cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Bakanna Kolopajú tun pin Bode odo pẹlu Venezuela, Jamaica, Haiti, Dominiki olominira, Honduras, Nicaragua àti Costa Rica..
wikipedia
yo
Pelu iye awon eniyan to to ẹgbẹgbẹ̀rún 45, Kolopajú ni iye eniyan 29th títóbijulo lagbaye ati ikeji títóbijulo ni guusu Amerika, leyin Brazil..
wikipedia
yo
Agbegbe ti a n pe ni Kolopajú loni kọ́kọ́ jẹ́ ibùgbé àwọn ará Abibíbí bí Muisca, Ppubáyà, ati Tairona..
wikipedia
yo
Awọn ará Spéìn débẹ̀ ni 1499 wọn si bẹ̀rẹ̀ ìsègùn àti iṣẹ́̀síwẹ́wẹ́, wọ́n fikúpa tàbí ṣe ìkólẹ́rú bí 90% àwọn ènìyàn ibẹ̀, nírúkọ ni wọ́n ṣẹ̀dásílẹ̀ ibá ilẹ̀ Grenada tuntun (tó ní ilé ìṣe Teli, Venezuela, Ecuador, ariwaiwoorun agbègbè agbègbè ilẹ̀ Brazil àti Panama) pẹ̀lú olúìlú rẹ̀ ní Bogotá..
wikipedia
yo
Ìlọkópa látọwọ́ Spain wáyé ní 1819, ṣùgbọ́n ní 1830 “Gran Colombia” dàrú èyí fa kí Venezuela àti Ecuador ó pínyà sọ́tọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn tí a mọ̀ loni bi Kolopajú àti Panama di orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Grenada tuntun..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè tuntun yí ṣèdánwò ìjọba Isealápapọ̀ gẹ́gẹ́ bí Ijosepapọ̀ Grenada (1858), àti lẹ́yìn rẹ̀ bí Ìparapọ̀ Àwọn Ìpínlẹ̀ Kolopajú (1863), kí o to dipé wọ́n kéde orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Kolopajú nígbẹ̀yìn ní 1886..
wikipedia
yo
Francisco De Miranda lo kọkọ lọ lati fi tọ́kasí gbogbo ilẹ̀ àgbáyé tuntun..
wikipedia
yo
Ní 1819 Gran Kolopajú gba bi oruko re nigba tó jẹ́ dídádásílẹ̀ Látinú àwọn agègbe ] kéèalTY of New Granada tẹ́lẹ̀ (Kolo, Panama, Venezuela ati Ekutóò loni).Jeografi B Kroko ní Bode ní ilá mọ́ Venezuela ati Brazil; ní gúúsù mọ́ Ecuador àti Peru; ní àríwá mọ́ Panama àti omi-okun Karidúdú; Beṣini ni iwoorun Mo ekuwọ ati okun Pasifìkí.1] wa ni ibi tí ibi ti an pé òrùka Pasina, ibi iletiwa, ibi ijo imin at imin àti Okeìléru, ó tún ní àwọn òkè 1994. Àwọn Oke-1] Àwọn ọdún 10,000 Kami 10,000 àwọn àwùjọ àti pẹ̀lú pẹ̀lú pẹ̀lú pẹ̀lú ẹmọ́ wà ní Bogotá (ní "el ábrá ní "Egbi-Q] àti wọ́n ṣṣòwò̀ pẹ̀lú ara wọn àti àwọn àwùjọ yìí ní àfonífojì ọ̀kọ̀we lati àfonífojì Ọ̀lati àwọn oníka mọ́ ní àfonífojì York.. Àwọn ẹ̀ka ohun Elita ni gbogbo ti ọdún rẹ̀. ↑ pẹ̀lú àwọn onímọ̀ ní gbogbo orin York ní pẹ̀lú omi (2] ní pẹ̀lú omi * ní ọdún gomina-s ] ní ọdún rẹ̀ sí àwọn òṣẹ ní Àfonífojì York. Àwọn oníẹ̀ kan ní àpá orin ( ] N ti ọdún 10. ati pẹ̀lú ọdún (s- ] Ní ọdún York. ↑ Ẹ dá àwọn agé omi * ọdún * * mọ́ ọdún York- ] Àwọn ès kan ní ọdún tí ọdún Nàìjíríà ní àwọn fi àwọn ọmọ * * ọdún **** fi ẹ̀ sí
wikipedia
yo
Bẹrẹ ni ẹgbẹ̀rúndún akọkọ Kj, awọn àdìpọ̀ awọn ọmọ Àmẹ́ríńdíà sedagbasoke Sistemu oloselu to n jẹ "CAcicazgo" pẹlu opo agba bi PiraMidi, yun látòkè wá sísàlẹ̀ tí àwọn olori rẹ únjẹ "CAcique"
wikipedia
yo
Nínú Kolopajú àwọn àṣà méjì pẹ̀lú Sistemu CAcicazgo lilọ́jújulọ ní àwọn Néyrọ́nà ní agbègbè KariHana, àti àwọn Mukà níbi àwọn ilé layika Bogotá, àwọn méjẽjì tí wọ́n jẹ́ ti ẹbí èdè Chibcha..
wikipedia
yo
Àwọn Rekáká ni wọ́n jẹ́ gbígbà bí àwọn tí wọ́n ní síste olóṣèlú Adàgbàsókè jùlọ ní Guuṣùù Amẹ́ríkà lẹ́yìn àwọn Inká.Ìri, ìbòrí àti ìmúnisìn látọwọ́ àwọn ará Spepe àwọn olúwa ará Spéìn gúnlẹ̀ sí Etiodo gúúsù KariHana ní 1499 pẹ̀lú Rodrigo dé Bsti bi Olórí wọn..
wikipedia
yo
Christopher Columbus gan ná wa ọkọ̀ ojú omi kọjá lẹ́gbẹ̀ KariHana ní 1502..
wikipedia
yo
Ní 1508, Vasco Nuñez De Balboa bẹ̀rẹ̀ síní ṣe ìjàborí àwọn agbègbè uraba..
wikipedia
yo
Ní 1513, ohun ní ara Europe àkọ́kọ́ tó dé okùn pàsífìkí, èyí tó pè ní Mar del Sur ("omi-òkun Gúúsù"), nípa báyì ó sí ọ̀nà fún àwọn ará Spéìsí yìókù láti lọ sí Peru àti Tsile..
wikipedia
yo
Gbogbo agbègbè yí ni àwọn ẹ̀yà bí àwọn ChibChan àti àwọn Carib, àwọn yí tí àwọn ará Spepéìn borí díẹ̀díẹ̀ bóyá pẹ̀lú ìjagun tàbí nípa ìbárẹ́pọ̀, nígbàkaná, àwọn àrùn tí àwọn ará Europe mú wá pẹ̀lú wọn, bí Sopanna, àti ìjà ìbòrí àti ìpalẹ̀mọ́ ẹ̀yà ènìyàn tó ń ṣẹlẹ̀, fá díẹ̀díẹ̀ kí àwọn olùgbé àbínibí ibẹ̀ ó ìdin púpọ̀..
wikipedia
yo
Ní Ọ̀RÚNDÚN 16th àwọn ará Europe bẹ̀rẹ̀ sí ní mú àwọn ẹrú wá lati Afrika.ìgbòte lọ́wọ́ Spéì lẹ́yìn ìbòrí K̀b lọ́wọ́ àwọn ará Spéìn àti igba písin olùìmúnisìn lọ́wọ́ wọn, ọ̀pọ̀ ẹgbẹ́ ìrinkan lọ lati gba ìdáwà tàbí ìlòdídán patapata agbègbè orílẹ̀-èdè
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ni àwọn wọ̀nyí ni àwọn ará Spéìn fi jàgídíjàgan kọ́ nílẹ̀, bẹ́ síni àwọn míràn nínú wọn kò ní agbára tó láti mú ìyípadà wá..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ Aarinkan fun Ìlọlọ́mọ to gbeyin bẹ̀rẹ̀ arin ọ́nni, lẹ́yìn ìgbà ti Saint Covgue (Haiti lọni) gba ìlòẹ̀yẹ ní 1804..
wikipedia
yo
èyí fu ìtìlẹ́yìn gidi fun àwọn tó ṣolori ìjídìde ní Kologis, yun Simon Bolivar àti Francisco de Paula Santander..
wikipedia
yo
Bolivar di Ààrẹ àkọ́kọ́ orílẹ̀-èdè Kolotà alómìnira lẹ́yìn ìjàbori ni ìjàogun bóyáca, lẹ́yìn tí Bolivar fipò yí sílẹ̀, Santander tó jẹ́ igbákejì rẹ̀ di Ààrẹ Ikeji orílẹ̀-èdè Kololéfòó..
wikipedia
yo
Adìde yí parí láìsírere ní 1819, nígbàtí ibawó ilẹ̀ Grenada tuntun bọ́ sí owó Orílẹ̀-èdè Olómìnira Kolopajú tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ dásílẹ̀ ngbaná bí Ìsọ̀kan Ekuaṣálẹ̀, Kobàbàrere àti Venezuela..
wikipedia
yo
Panama nígbànã jẹ́ apá ilẹ̀ Kolopajú.Ìjọàwọn ìpín àmójútó Kolopajú jẹ́ pípín sí àwọn 32 Ìpínpa 32 àti agbègbè ìlúìlú kan, tí wọ́n mú bí ìpínpa kan (Bogotá nã tún jẹ́ olúìlú fún Ìpínpa Cundínàca)..
wikipedia
yo
Àwọn ìpínpa nã tún jẹ́ pínpínlábẹ́ sí àwọn múnisípál, ìkọkan wọn tó ní ibùjókò múnisípál, bákannã àwọn múnisí tún jẹ́ pípínbẹ sí Corrẹ́gí!
wikipedia
yo
Ìpínpa kọkàn ni Ìjọba ìbílẹ̀ pẹ̀lú Gómìnà àti Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin ti wọn n jẹ dídìbòyán tara sí igba ọdún mẹrin..
wikipedia
yo
munista kọọkan ni Baálẹ̀ ati Igbimọ, Be Sínì Corrẹ́gí26 kọọkan ni Corrẹ́gídor, tabi Olori ibile.Lapapọ mo oluilu, awọn ilu miran na tun wa ti pe ni agbegbe, nitori ini pataki ti wọn ni..
wikipedia
yo
Àwọn wọ̀nyí ni Barranquilla, Cartage, Santa Marta, CucUta, Popayan, BuCaramanman, tunja, turbo, Sẹ́mevenven àti Tuìkógunìkógun..
wikipedia
yo
Àwọn apáìpín ní ìpínabẹ ìbílẹ̀ àmójútó, níbi tí àwọn ìlú ní àwọn olùgbé tó tóbi tí wọ́n sì wà nítòsí ara wọn (fún àpẹrẹ ní Antioquia àti Cundínàmarca)..
wikipedia
yo
Ní tó bá jẹ́ pé àọ́n olùgbé kéré ṣùgbọ́n wọ́n ní ÌṢÒRO àbọ̀ (fún àpẹgbò Amazonas, Ìdádidínlógójì àti VichaDA), ìpín àmójútó pàtàkì jẹ́ lílò, bí "apá Corrẹ́gí Corrhon", tó jẹ́ Àpọ̀pọ̀ ìlú àti Corré te K\ sórí apá apá kan lórí máàpù láti wípé àyọkà mí.Ọ̀rọ̀ Okere àwọn ọ̀rọ̀ Okere ilẹ̀ Kosha jẹ́ Látọwọ́ Ààrẹ ilẹ̀ KoKrístì sí Pdara kí kò Látọwọ́ Alá Ọ̀rọ̀ Okere..
wikipedia
yo
(Kísẹ ibujoko sí organization of American States.[1] je omo egbe Àgbájọ awon orile-ede Andes ati isokan awon orile-ede guusu Amerika.Awon ara Kolopajú gbodo gba VV olùbẹ̀wò fun awon orile-ede 180 lati lo si be and DO not need Tourist V for 15 countries.Aboyọjútofìkíifwonjiji..
wikipedia
yo
30 AD/ce), tàbì Jésù Kírísítì tàbí Jésù, jẹ́ ẹni tó ṣe kókó jùlọ, yàtọ̀ sí Ọlọ́run nínú ẹ̀sìn Kírísítì, tí àwọn ẹlẹ́sìn náà gbà gẹ́gẹ́ bí Olùgbàlà aráyé, èyí tí ó jẹ́ àsọtẹ́lẹ̀ ní Májẹ̀mú Láéláé nínú Bíbélì, ti gbogbo àwọn ẹlẹ́sìn Kiyínjè tàbí irú wọn gbà pé òun ni Ọmọ Ọlọ́run àti àwòrán Ọlọ́run tí ó jí dìde nínú ipò òkú..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀sìn mìíràn ni wọ́n tún tẹrí ba fún un lórílẹ̀ ọ̀nà..
wikipedia
yo
Jesu jẹ́ ẹnìkan tó ṣe pàtàkì nínú ìtàn ọmọ ènìyàn.Ẹ tún lè ka ọmọlẹ́yìn (ní Kristẹni) Josẹfu mímọ́àwọn ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 0àwọn Ọjọ́aláìsí ní 30 ìgbésíayé..
wikipedia
yo
Michael Jeffrey Jordan (Ọjọ́ìbí February 17, 1963) je agba boolu Alaobare omo ilẹ̀ Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ọmọ Áfríkà AmeriWọn agbaboolu alapere ara Ameria tó gba eso Wúrà látinú Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
1809 – December 31, 1891) jẹ́ onímọ̀ èdè Yorùbá àti Bíṣọ́ọ̀bù àkọ́kọ́ fún Ìjọ Anglican lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O je omo bibi ilu Ooso(ibi ti a pada mo si ilu Ado-awa) ni ijoba ibile Iyín ni ipinle Oyo..
wikipedia
yo
Àwọn olówó ẹrú Fúlàní kó ohun àti ìdílé rẹ̀ Meru nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún méjìlá..
wikipedia
yo
Eleyi ṣẹlẹ̀ nígbà ogun abẹ́lé ẹ̀yà Yorùbá, papàá jùlọ àwọn ogun Ìlú Ọwọ́(1821-1829), wọ́n sì padà táa fáwọn Olówó Ẹrú Portuguese..
wikipedia
yo
Níbi tí wọ́n ti gbé lọ sínú ọkọ̀ju omi ní Odò Atlantic tí ó ùn lọ sí ìwọ̀ Oòrùn àgbáyé.Àwọn Royal Navy’s West Africa Squadron tí wọ́n ún ṣiṣẹ́ fún British láti fò pín sí ìkónilẹ́rú tú Crowther sílẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n kó àwọn ènìyàn tí wọ́n tú sílẹ̀ sí orílẹ̀-èdè Sierra Leone..
wikipedia
yo
Ní Sierra Lone, Àjàyí fi Samuel Crowther ṣe orúkọ ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó sì tún bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ òyìnbó..Àjàyí di Christẹni ó sì tún bẹ̀rẹ̀ sí un pe ara rẹ̀ ní ọmọ ẹ̀yà Krio ní orílẹ̀-èdè Sierra Leone..
wikipedia
yo
Ó kó ìmọ̀ èdè, wọ́n sì tún padà sọ Mínísítà ní England, níbi TiVo padà gba àmì-ẹ̀yẹ Dókítà ní Yunifásítì ìlú Oxford..
wikipedia
yo
Ó ṣe ògbufọ̀ ìwé àdúrà Anglican sí èdè Yorùbá, ó sì tún ṣiṣẹ́ lórí ògbufọ̀ Bíbélì lati èdè òyìnbó si Yorùbá.Ìdílé rẹ̀Samuel Crowther jẹ́ Ọmọ-ọmọ Ọba Abiodun, ẹni ti ó jẹ́ baba ìyá rẹ̀..
wikipedia
yo
Àjàyí jẹ́ ọmọ ọdún méjìlá nígbà tí àwọn akónilẹ́rú Fúlàní kó ohun, ìdílé rẹ̀ àti àwọn ará abúlé rẹ̀ ní March 1821 tí wọ́n sì tà wọ́n fún àwọn Olówó-ẹrú Portuguese..
wikipedia
yo
Ìyá rẹ̀, Afale, ẹni tí a padà fún ní orúkọ Hannah nígbà tí a ṣe ìtẹ̀bọmi fún, àbúrò rẹ̀ ọkùnrin, àti àwọn ìdílé rẹ̀ wà lára àwọn tí wọ́n kọ́..
wikipedia
yo
Àyèmi nígbà rí wọn kógun ja abúlé rẹ̀ tàbí lẹ́yìn ìgbà díẹ̀ tí ìṣìlè náà ṣe.Àwọn British fòfinde ìkónilẹ́rú gba okùn Atlantic ní ọdún 180u, wọ́n sì fi àwọn ọmọ ogun ojú omi wọn mú kí òfin náà wá sí ìmúṣẹ..
wikipedia
yo
Ni igbayẹn, orile-ede Spain ati Portugal si fi aye gba kíkó ni lẹ́rú lọ si orile-ede Amerika..
wikipedia
yo
Kí ọkọ̀ ojú-omi náà tó fi eti odó sílẹ̀ lọ sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, àwọn ọmọ ológun Ọ̀dọ́ ti Britain wọ ọkọ̀ náà pẹ̀lú wọn, lábẹ́ àṣẹ Captain Henry lẹ́ẹ̀ter..
wikipedia
yo
Wọ́n tún àwọn ẹrù náà kalẹ̀, wọ́n sì kó Ajayi àti ìdílé rẹ̀ lọ sí Sierra Leone, níbi tí àwọn olórí ibẹ̀ ti fi wọ́n sí ibi tí wọ́n ò bugbe sí.Àwọn ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1809àwọn Ọjọ́aláìsí ní 1891àwọn ọmọ Yorùbá..
wikipedia
yo
O jẹ ilu ebute ni eti okun Atlantiki to bùdó si agbegbe apaiwoorun ile Sierra Leone pẹlu kerindinlogboneniyan to je 1,070,200.itọkasi awon oluilu ni Afrika..
wikipedia
yo
Èrò ìléwọ́ ìbánisọ̀rọ̀ jẹ́ ohun èlò ẹ̀rọ ìgbàlódé ti ẹni méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ le fi bá ara wọn sọ̀rọ̀, yálà nípa ohun tàbí ìkọ̀wé ránṣẹ́ sí ara wọn, bí wọ́n bá tilẹ̀ wà lọ́nà jíjìnnà réré sí ara wọn..
wikipedia
yo
Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ tí ẹ̀rọ yìí wà fún ìbánisọ̀rọ̀ nìkan, ṣùgbọ́n ìmọ̀ ti gorí ìmọ̀, ẹ̀rọ ìléwọ́ ìbánisọ̀rọ̀ ti wà fún oríṣiríṣi nǹkan ju ìbánisọ̀rọ̀ lásán lọ.Ìtàn ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ìgbàgbọ́ lórí ìwàrìí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ dúró sí àríyànjiyàn..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú òmíràn rídò ń la irú bí Mojahùn, ina Gilobu àti Kọ́mùire..
wikipedia
yo
Orísirísi àwọn olùdásílẹ̀ tó ṣe aṣájú iṣẹ́ ìdánwò lórí àtagbà ohun lórí okùn-irin àti atún-ṣe lórí ìrò ọ̀kọ̀ọ̀kan mìíràn..
wikipedia
yo
Antônio Ucci, Johann Philipp rẹ̀is, Elisha Gray, Alexander Graham Bell àti Thomas Edison, nínú àwọn òmìíràn, gbogbo wọn ti gba ìyìn pẹ̀lú iṣẹ́ àsájù lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀.Ìtàn ìbẹ̀rẹ̀ ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ jẹ́ èyí tí ó ní anjìyàn, tí ó dabarú irá ti ẹ̀tọ́..
wikipedia
yo
Ipasẹ̀ àkópọ̀ àwọn ẹjọ́ ni wọ́n fi pinnu àwọn eré sílẹ̀ nígbangba fún àwọn ènìyàn..
wikipedia
yo
Àwọn Bell àti Edison ni wọ́n dá púpọ̀ nínú ìtàn ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀.Ìwúlò rẹ̀Ó wúlò nígbà tí nǹkan àìkíkú bá ń ṣe lé ó ń gba ènìyàn là nínú ewu..
wikipedia
yo
Tíátà jẹ́ ọ̀rọ̀ tí ó wáyé láti inú èdè Gírìíkì tí ó túmọ̀ sí ibi ìwòran ó sì tún ní ẹ̀ka bí eré ìtàgé tí ó túnmọ sí pé, nígbàtí ènìyàn kan tàbí jù bẹ́ẹ̀ bá kó ara wọn jọ ní àkókò kan tàbí sí ibìkan láti dá àwọn ènìyàn lárayá..
wikipedia
yo
Nípa ìtumọ̀ tí ó gbòòrò yí, láti ìgbà tí ènìyàn ti wà láyé ní tíátà ti wà tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ tí ó ṣe ṣàjúwe ìgbé ayé ènìyàn nítorí ìfẹ́ àwọn ènìyàn sí ìtàn sísọ..
wikipedia
yo
Láti lẹ̀ṣẹ̀ tíátà, ni ó ti ń mú oríṣìí ará Dani..
wikipedia
yo
A sì maa n lo awon èròjà bi oro, ìisesi, orin, Ijo ati Ìwòran papo mo eré itage sinu Tiata..
wikipedia
yo
Tíátà ayé ìsinsìnyí ni ó tún kún fún òtítọ́ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó pín sí oríṣìíriṣí ọ̀nà.Tíátà àkọ́kọ́ ní a ṣe ní ẹgbẹ̀rún ọdún méjì ṣãjú ikú Olúwa wá sẹ́yìn, ní ó jẹ́ èrè ìtara nípa ilẹ̀ ígíbítì ìgbani..
wikipedia
yo
Ìtàn nípa Ọlọ́run orisiri ni wọ́n fi ń se tíátà ní ọdọdún láti sin ọlọ́run Ósírísì wón yí títí di ìgbà ye ọ̀làjú, èyí wá fi hàn nípa ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàrín tíátà àti ẹ̀sìn..
wikipedia
yo
Awon ara Giriki akoko ni o koko se agbekale Tiata gege bi ise, won si tunmọ Tiata si orisiri ona bi ere ti Adùn keyin re, ere ti ibanujẹ keyin re ati ere ti o se apejuwe awujo..
wikipedia
yo
Sugbon laye ode oni, Tiata sise ti gba igba otun, ti a n se sinu fanran fun agbelewo awon eniyan fun igbadun..
wikipedia
yo
Tíátà àṣà àti ìṣe tí àwọn òṣèré máa ń lò láti ṣe ìgbélékè àṣà àti iṣẹ́ tí ó ti dòkú, pàápàá ní ilẹ̀ Áfíríkà..
wikipedia
yo
Nipa tíátà ni a ti mọ̀ pàápàá ni ilẹ̀ Yorùbá àwọn àṣà ati ìṣe wa, tí ó ti sọnù nítorí àṣà àti ìwà àwọn oyinbo ti gba àṣà àti ìṣe wa lọwọ wa..
wikipedia
yo
Ọ̀kan ninu ìsọ̀rí tíátà ni, tíátà nípa àwùjọ àti òṣèlú..
wikipedia
yo
Tíátà nípa àwùjọ ni àwọn eléré ìtàgé fi ń ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àyípadà sí àwọn àlèbù àti kùdìẹ̀-kudiẹ tó kú nínú àwùjọ wa lónìí..
wikipedia
yo
Ní tíá ṣiṣẹ́ bólà nípa eré ìtàgé tàbí ti àgbéléwò ni àkò ti n bá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ayé tí ó wà ní ìkóríta ìríjú, tí wọ́n kò sì mọ́ ohun tó yẹ láti ṣe..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ olóṣèlú ni bá ti sọ ayé di tàwọn nìkan, bí kò bá sí ti àwọn àleré ìtàgé tàbí ti àgbéléwò tí òún Pi ìwà ìbàjẹ́ wọn lédè..
wikipedia
yo
Tíátà tí ó ti wá láti bí ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn, ló ti gbà àtúnṣe nípa ìdàgbàsókè tí ó ti dé báa ní ayé òde òní..
wikipedia
yo
Tíátà síṣe yálà ti eré ìtàgé tàbí ti àgbéléwò ló wà fún ẹ̀kọ́, ìtọ́sọ́nà àti fún ìṣàtúnṣe àwùjọ tí a wà lónìí.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Panama, fún tóníbiṣẹ́ bí Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ilẹ̀ Panama (; ), jẹ́ Orílẹ̀-èdè ní àrin Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
‘Iṣẹ́ àgbẹ̀’ jẹ́ iṣẹ́ kan tí à ń ṣe láti fi gbin ohun ọ̀gbìn tàbí irè oko tàbí sísìn ohun ọ̀sìn láti fi bọ́ ènìyàn àti ẹranko.Yorùbá gbàgbọ́ pé, iṣẹ́ àgbẹ̀ jẹ́ iṣẹ́ ilẹ̀ wa..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ju èyí lọ, iṣẹ́ àgbẹ̀ ti wà láti ìgbà tí ayé ti wà..
wikipedia
yo
Bí a bá sì ń sọ nípa ọ̀rọ̀ àgbẹ̀, kìí ṣe iṣẹ́ oko nìkan là ń sọ..
wikipedia
yo
Kò sì sí ọ̀kan ninu ìsọ̀rí iṣẹ́ àgbẹ̀ yí tí kò ní èrè tabi anfani fún olórí-kò-jorí, fún àwùjọ, fún àwọn ilé-iṣẹ́ ati fún orílẹ̀-èdè lápapọ̀..
wikipedia
yo
Kí a kúkú sọ pé, Láísì iṣẹ́ àgbẹ̀, kò lè sí ènìyàn nítorí pa oúnjẹ ní ore awọ.Àwọn ọ̀nà tí a ń gbà ṣiṣẹ́ Agbéni ayé àtijọ́ àwọn àgbẹ̀ lọ́jọ́ṣẹ́ nìkan ni ó wà, ṣùgbọ́n láyé òde òní iṣẹ́ àgbẹ̀ ti gbọ́únjẹ fẹ̀gbẹ́ ó sì ti gbawọ́ bọ̀..
wikipedia
yo
Lónìí àti rí àgbẹ̀ AlaGalileo-nlá, alápapọ̀ ṣe, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lópàtàkì àti ìwúlò iṣẹ́ Agbéni ilẹ̀ Aláwọ̀-dúdú àti ní Àgbáyé lápapọ̀, ara àwọn pàtàkì iṣẹ́ àgbẹ̀ ni pé, nípa iṣẹ́ àgbẹ̀ ni àti máa ń mú oúnjẹ jáde fún gbogbo ènìyàn àti fún àwọn ẹranko pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Láìsí oúnjẹ yóò ṣòro fún ènìyàn láti máa gbé ní àlàáfíà, nítorí pé okun tinú la fi ń gbé títà..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ àgbẹ̀ ní ń mú oúnjẹ wá; oúnjẹ ní sì ń mú ìlera wá, ara-líle sì ni ogún ọrọ̀..
wikipedia
yo
Ó túnmọ̀ sí pé, láìsí iṣẹ́ àgbẹ̀ tó jẹ́ orísun ìpèsè fún ohun àmúlò ilé-iṣẹ́ ńlá àti kékeré, láìsí àwọn ohun àmúlò wọ̀nyí kò le ṣe é ṣe fún ilé iṣẹ́ láti máa ṣiṣẹ́..
wikipedia
yo
bí kò bá sí ilé iṣẹ́, kò ní sí iṣẹ́ fún àwọn eniyan láti ṣe..
wikipedia
yo
èyí tí ó tún túmọ̀ sí pé, iṣẹ́ àgbẹ̀ jẹ́ ọ̀nà sí ìpèsè iṣẹ́ fún àwọn ènìyàn..
wikipedia
yo
Nínú àbájádeẹ̀ àwọn aláyẹ̀wò nípa iṣẹ́ àgbẹ̀, wọ́n sọ pé, ó tó ìpín bí ọgọ́ọ̀rin ènìyàn tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ ní ọ̀nà kan tàbí òmíràn nípa iṣẹ́ àgbẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n pẹ̀lú àwọn ànfàní tí ó kóra jọpọ̀ sínú iṣẹ́ àgbẹ̀ yí, àwọn ènìyàn sì kóòríra iṣẹ́ àgbẹ̀ síbẹ̀.Kí ni ìdí tí àwọn ènìyàn fi yan iṣẹ́ àgbẹ̀ ní posinlára àwọn ìdí tí àwọn ènìyàn fi ní ìkóòríra sí iṣẹ́ àgbẹ̀ nipé, ó jẹ́ iṣẹ́ tí ó nira láti ṣe..
wikipedia
yo
Láì fi ìgbà bọ̀ kan nínú rárá, iṣẹ́ àgbẹ̀ jẹ́ iṣẹ́ tí ó nira, ìdí nìyí tí àwọn ènìyàn fi ń sá fún iṣẹ́ yí nítorí pé kò sẹ́ni tí ó fẹ́ ṣiṣẹ́ tó nira rárá, a fi iṣẹ́ ìrọ̀rùn nìkan, bí iṣẹ́ ọ́fíìsì..
wikipedia
yo
Àwọn ohun èlò tí wọn ń lò, bíi àdá ati oko tún ń ba àwọn eniyan lẹ́rù láti fi ṣiṣẹ́ agbe..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n nígbà tí ọ̀làjú dé, ni àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ohun èlò amáyédẹrùn fún iṣẹ́ àgbẹ̀..
wikipedia
yo
Èyí ló wá mú kí iṣẹ́ àgbẹ̀ wa wú ọ̀pọ̀lọpọ̀ láti ṣe, nítorí pé kò wá sí àṣẹ́kù ní iṣẹ́ àgbẹ̀ nítorí ìrànlọ́wọ́ kẹ́míkà tí a fi n pa ọkọ́ àti àwọn ohun èlò ìgbàlódé míràn bí èyí tí wọ́n fi ń kòkó, èyí tí wọ́n fi ń kórè àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú ìdàgbàsókè tí ó ti bá iṣẹ́ àgbẹ̀ ní àwùjọ wa lónìí yìí, ó yẹ kí ẹní kọ̀ọ̀kan wa mú iṣẹ́ àgbẹ̀ yí lọ́kùnkúndùn-ún nítorí nípa iṣẹ́ àgbẹ̀ ní oúnjẹ fi lè pọ̀ yanturu ní àwùjọ wa..
wikipedia
yo
kìí ṣe bẹ́ẹ̀ nìkan ṣùgbọ́n ó tún jẹ́ ọ̀nà láti tàn òṣì àti ìṣẹ́ nípa pípèsè iṣẹ́ fún àwọn tí kò rí iṣẹ́, yó sì tún mú ìdàgbàsókè bá ọrọ̀ ajé wa ní orílẹ̀-èdè wa, Nàìjíríà àti àgákó lápapọ̀.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àni tàbí orílẹ̀-èdè òtòsí onímàlè ilé àni jẹ́ orílẹ̀-èdè ní apáwà Éṣíàìtọru láẹ̀-ẹ̀kun..
wikipedia
yo
Edgar Douglas Adrián níjọ̀jọ́ Oṣù Kọkànlá Ọdún 1889 (11-30-1889)..
wikipedia
yo
Ó kú ní ọjọ́ kẹrin Oṣù kẹjọ ọdún 1977 (ní ìgbà náà ó jẹ́ ọmọ dùn mẹ́ta-di-ní-àádọ́rùn-ún).Ó jẹ́ ará ìlú British tí ó jẹ́ onímọ̀ ìfẹ́rọ mọ́-iṣẹ́-ohun-ìmi àti Olugba ẹ̀bùn Ibibiye ọlọ́lá ní ọdún 1932 fún ìmọ̀ iṣẹ́ ohun ìmi tí òun àti Sir Charles Sherrigbọ̀n jùmọ̀ jẹ́ fún onímúlò òun kan nínú ará tí ó ma gbé ìròyìn láti ibi ọpọlọ dé ibi-tí ó kú lára..
wikipedia
yo
Ọmọ Alfred Douglas Adrián, Onimọ̀ràn òfin fún ìgbìmọ̀ ìjọba ìbílẹ̀ ti Bakotunsi (British) ní ọ̀jọ̀gbọ́n Edgar jẹ́..
wikipedia
yo
Ọ̀jọ̀gbọ́n edger Adrián lọ si ile-iwe West Minister, ó sì ka sáyẹ́nsì àdánda ní ilé-ìwé gíga ti Kemiji..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ àṣeparí fún ẹ̀kọ́ wọn ti ilẹ̀-wòsàn ni ó ṣe ní ilé-ìwòsàn ti St..
wikipedia
yo