cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ado Ekiti je ilu nla kan ni apa iwo oorun orile-ede Naijiriati o si je olu-ilu fun ipinle Ekiti.titobi ati bi ero se po nibegege bi eto ikaniyan ti odun 2006 se so wipe apapo iye awon eniyan ti won n gbe ni ilu Ado Ekiti yálà Yoruba Ekiti ni, tabi ẹya miran je 308,621, bi o tile je wipe awon Ekiti látòkè Dele je okan lara eya Yoruba, amo ti won tun tan die mo Edo..
wikipedia
yo
Edo-Ekiti tabi Ado-Ekiti ni awon Yoruba ma n saba pe eni ti o ba wa lati Ipinle Edo tabi Ado..
wikipedia
yo
Ohun ti o faa ni wipe asa ati ise won wonu ara won bi Eégún ti wonu ẹran..eto Eko Ibeilu Ado ni ile-eko ti ijoba ipinle ti won n pe ni Yunifasiti Ado Ekiti amo ti won ti yi pada si Ekiti State University..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ìlú náà tún ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì àdáni tí ó ń jẹ́ afẹ́ Babalola University tí ó wà ní ìlú Adó-Èkìtì, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n tún ní ilé-ẹ̀kọ́ àkọ́ṣe-mọ́ṣẹ́ pọ̀pọ̀ tí ó jẹ́ ti ìjọba àpapọ̀ tí wọ́n pè ní Federal Polytechnic, Adó-Èkìtì, wọ́n sì tún ní ilé-ẹ̀kọ́ ti Gbogbonìṣe Poli ti aládàáni tí wọ́n pè ní crown Polytechnic, Odò, Adó-Èkìtì ọ̀rọ̀ Ajé wọnlára àwọn ọ̀bùn tí wọ́n fi ń sọ̀rọ̀ Ajé ní ìlú Adó-Èkìtì ní kí a gbóhùn sáfẹ́fẹ́, lára àwọn ilé-iṣẹ́ ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ tí ó jẹ́ amóhùmáwòrán-máwòrán ti ìjọba Àpapọ̀ Nigerian Television Authority (NTA) tí ó wà ní ìlú Adó-Èkìtì..
wikipedia
yo
Bákan náà ni wọ́n tún ní ilé-iṣẹ́ amórónì-máwòrán ti ìpínlẹ̀ tí wọ́n pè ní Èkìtì State Television (Bses)..
wikipedia
yo
Ilu Benin tabi Benin City jẹ ilu ni Naijiria ati oluilu ipinle Edo.Gallery ipinle Naijiria..
wikipedia
yo
Ralph Waldo Ellison (March 1, 1914 – April 16, 1994) jẹ́ olùkọ́ àti Olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà.Àwọn Ìtọ́kasíEllison Ralphàwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Alex Ifeanyichukwu Ekwúeme (Ọjọ́ìbí October 21, 1932) jẹ́ olóṣèlú àti igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà sí Ààrẹ Shehu Shagari ní ìgbà òṣèlú kejì lati 1979 de 1983.Ìtọ́kasí Àwọn Igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
EZ DrNOV (May 17, 1950 – February 23, 2008) a bi ní ọdún 1950..
wikipedia
yo
O si di ọmọ ile asofin ile SLOVENIA ni odun 1986..
wikipedia
yo
IṢẸ́ ribiribi ni ó ṣe láàrín ọdún mẹ́wàá tí ó fi ṣe olóòtú ìjọba..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ kí àyàn ẹ̀ẹ́ dara pọ̀ mọ́ European Union àti Ntọ̀ ní 2004..
wikipedia
yo
Oṣu kejila ọdun 2007 bi o fi ipo are ilẹ̀ Slovenia silẹ..
wikipedia
yo
O ku nigba ti o di ọmọ ọdun mẹ́tàdínlọ́gọ́ta.org..
wikipedia
yo
Muhammad Yunus (, pípẹ́ ) (ọjọ́ìbí 28 June 1940) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Bangladesh..
wikipedia
yo
Nígbà tí òun náà dàgbà, ó di ilé-ìfowópamọ́ tí a ti lè máa yá àwọn òtòṣì lówó sílẹ̀..
wikipedia
yo
Irú bánkì yìí ni í wá di Community Bank lóde òní Mohammed Yunus ló kọ́kọ́ dá a sílẹ̀..
wikipedia
yo
Yunus ti ní irú báńkì yìí nínú abúlé tó tó 35,000 nínú abúlé 68,000 tí ó wà ní Bangladesh..
wikipedia
yo
Òun ni ó gba ẹ̀bùn Nobel ti 2006Ìtọ́kasí àwọn ẹlẹ́bùn Nobel ara Bangladeshi..
wikipedia
yo
Napoleon Bonaparte (15 August ìràwọ̀ – 5 May 1821) jẹ́ olórí ológun àti adarí òṣèlú àti ọmọ bíbí ìlú Corsica ní ilẹ̀ Faransé..
wikipedia
yo
Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká ní àsìkò ìyípadà ìṣèjọba ilẹ̀ Faransé, tí ó sì léwájú àwọn ígbara oríṣiríṣi ní àsìkò ogun..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí Napoleon í, òun ní ọba ilẹ̀ Faransé láti ọdún 1804 sí ọdún 1814, àti 1815..
wikipedia
yo
Napoleon se akoso ijoba ile Yuroopu ati agbaye fun bi odun mewa, nigba ti o n lewaju ninu awon ogun orisirisi ti a mo si Nunileonic wars..
wikipedia
yo
Ó ja ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun, tí ó sì borí àwọn ogun tí ó sì mú láti gba àwọn ilẹ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ fún ìjọba Faransé, tí ó sì darí ilẹ̀ Yúróòpù lápapọ̀ ṣáájú kí ìjọba rẹ̀ tó ṣubú ní ọdún 1815..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn adarí ní orílẹ̀ àgbáyé tí wọ́n sì ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìṣèjọba rẹ̀ jákè-jádò àgbáyé..
wikipedia
yo
Ó sì wà nínú àwọn adarí tí ó gbayì jùlọ ní inú ìtàn àgbáyé.Ììtọ́ka sí àwọn Ọjọ́ìbí ní Àdúràpàwọn Ọjọ́aláìsí ní 1821àwọn ọba Fránsì..
wikipedia
yo
The Alliance broke Down in Rèbékà, which led to the French invòdòdó in 1812..
wikipedia
yo
During that time Russia wáged war against Sweden (1808-1809) and the Ottoman Empire (1806-1812), and Kailally went to war against Britain (1807-1812).Spain, an ally of France until a steìyàsọ́tọ̀ French inv] in 1808, defected and fought against France in the èpòsular war.Sicily Remained in personal Union with Naples until the latter became a French client-Republic following the battle of Campo tenese in 1806.2] Sweden declared declared war against the United Kingdom after its defeat by Russia in the Finnish war (180-2).the French Empire Anne] The Kingdom of Holland in Rèbékà..
wikipedia
yo
Dutch troops fought against Napoléon during the hundred days in 1815.The French Empire Anneamúnikún the Kingdom of Etruria in 1807.The Kingdom of Naples, briefly Allied with Austria in 1814, Allied with France again and fought against Austria during the Neapolitan war in 1815.Napoleon established the Duchy of Warsaw in 1807..
wikipedia
yo
Polish LéÁmórìs had already served in the French army beforehand.Six of France's Allies among the German states (including Bavaria and Württemberg) established the confederation of the Rhine in July 1806 following the battle of Austerlitz (December 1805)..
wikipedia
yo
Fog the battle of Jena-auers (October 1806), various other German states that had previously fought alongside the anti-French allies, including Saxony and Westphalia, also Allied with France and joined the confederation..
wikipedia
yo
Saxony changed sides once again in 1813 during the battle of Leipzig, causing most other member-States to quickly follow ètò and Declare war on France.Denmark Remained neutral until the battle of Copenhagen (1807).Ogun fàyèleoníjàgbara ti a n pe ni Revolution tí ó ṣẹlẹ̀ ní France jẹ́ ki fance ní Ota pupo ní ìlú oyinbo..
wikipedia
yo
Èyí ni ó sì fa ogun tí ó ṣẹlẹ̀ láàrín 1792 sì 1815 tí ó fẹ́rẹ̀ máa dáwọ́ dúró.Ní àsìkò ogun yìí, ilẹ̀ Faransé ni ọ̀gágun kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Napoleon Bonaparte..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó ti ṣẹ́gun wọ̀nyí, ó sọ ara rẹ̀ di Emperor ní 1804..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó ti di olórí ilẹ̀ Faransé tán ó tún fẹ́ di olórí gbogbo ìlú òyìnbó..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí, gbogbo ìlú òyìnbó ni ó wá gbógun tì í kí àbá rẹ̀ yìí má baà lè ṣẹ.Àwọn ìlú tó ń bá ilẹ̀ Faransé jà nígbà náà ni Austria, Prussia, Russia, Britain ati Spain..
wikipedia
yo
Àwọn eléyìí tí ó ṣe pàtàkì jù ní Ogún MareNGO àti HHengen ní 1800 ti Austerlitz ní 1805 àti ti Tìtẹnumọ́ ní 1806..
wikipedia
yo
Ìṣẹ́gun yìí fún Napoleon ní agbára láti máa darí ilẹ̀ ìlú Òyìnbó.Ṣùgbọ́n ṣá, àwọn ológun ojú omi ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì lágbára gan-an ni..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣẹ́gun ọmọ ogun ilẹ̀ Faransé ní ogun nílẹ̀ ní 1798..
wikipedia
yo
Inu bi Napoleon, ko je ki awon oja ile Geesi koja si awon ile ilu oyinbo miiran mo..
wikipedia
yo
Àìrí ọjà ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì yìí dá wàhálà sílẹ̀ fún àwọn ilẹ̀ yòókù..
wikipedia
yo
Ẹni tí ó ṣáájú ọmọ ogun ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ló ni Arthur WelLesley tí ó padà wá ń jẹ́ Duke of Wellington..
wikipedia
yo
Napoleon ṣígun lọ sí Russia ṣùgbọ́n gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ ni ó kì sí ohùn..
wikipedia
yo
Torí gbogbo ìṣẹ́gun wọ̀nyí, bsrĩmoni, Prussia, Sweden, Russia àti mélòória para pọ̀ láti bá ilẹ̀ Faransé jà..
wikipedia
yo
Ó sá àsálà ó sì wá bá ọmọ ogun Britain ati Prussia jà ni Waterloo..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣẹ́gun Napoleon wọ́n wá lé e lọ sí St Helena.Ìtọ́kasí àwọn ogun..
wikipedia
yo
Òun ni Chancellor West German Federal Republic ní 1949 sí 1963..
wikipedia
yo
Oun ni o da Chrismoni Democratic Party sile oun si ni Alaga re lati 1945 titi di 1966..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti ṣẹ́gun Jemani tán, ó fún Jemani ní òfin (Constitution) tí ó fi ní lọ́kàn balẹ̀ ó sì jẹ́ kí àwọn ìlú òyìnbó yòókù fún Jemani layé nínú ẹgbẹ́ àfọwọ́sowọ́pọ̀ (Western Alliance) wọ́n..
wikipedia
yo
Ó sa gbogbo agbára láti jẹ́ kí ìparí ìjà wà láàrin ilé Fránsì àti Jemani ṣùgbọ́n kò fi ayé (Accommodation) gba àÌtọ́kasí.Ìtọ́kasí àwọn kanlá ilẹ̀ Jemani..
wikipedia
yo
Kàlẹ́ńdà Gregory ní kàlẹ́ńdà tí ó ń jẹ́ lílò jùlọ kákiri.Ìtọ́kasí àwọn kàlẹ́ńdà..
wikipedia
yo
Oṣù jẹmọ́ ìgbà tàbí àkókò tí à ń lo ìwé-ìwọ̀ ọjọ́ fún tí àyípadà rẹ̀ sì máa ń pé bíi ojú ọjọ́ tí ó sì farapẹ́ bí òṣùpá ṣe ń ṣiṣẹ́..
wikipedia
yo
Oṣù àti òṣùpá ní ìbáṣepọ̀ tó dánmọ́rán.Kí a tólẹ̀ mọ bí oṣù ṣe ń ṣiṣẹ́, a gbọdọ̀ ní òye púpọ̀ nípa bí òṣùpá ṣe ń ṣiṣẹ́..
wikipedia
yo
òdiwọn ti òṣùpá àti Oṣù fi n ṣiṣẹ́ kojú “Ọkan dín lọ́gbọ̀n lọ́gbọ̀n sí mẹta lé laadota Ojo lo (29.53. Days.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ẹyọ asiko..
wikipedia
yo
Peoples Democratic Party [PDP] (Ẹgbẹ́ DemoBERTí Àwọn Aráàlú) jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Awon ni omo egbe won se ijoba apapo orile ede Naijiria titi di odun 2015 ki egbe oselu All Progressives Congress to gbàjọba apapo lowo won..
wikipedia
yo
Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; Olúsẹ́gun Ọbásanjọ́, Umaru Musa Yar'Adua àti Goodluck Jonathan ní ẹgbẹ́ yìí jẹ́ kí ẹgbẹ́ APC tó dá wọn lágbo nu lọ́dún 2015, tí Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ẹgbẹ́ APC fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ẹgbẹ́ olóṣèlú ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Alfred Adler jẹ́ oníṣègùn òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè Austria..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ oníṣègùn àrùn ọpọlọ tàbí wèrè (psychiatrist)..
wikipedia
yo
Òun ni ó dá ilé-ẹ̀kọ́ tí ó ń jẹ́ 'School of Examinal Psychology' sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀gbẹ́ni freud ni ó kọ́kọ́ ń tẹ̀ lé ṣùgbọ́n ó yapa kúrò ní ọ̀dọ̀ rẹ̀ lọ́dún 1911..
wikipedia
yo
Lójú rẹ̀, wàhálà ti ènìyàn ní láti sa agbára láti yọ ara ẹni kúrò ní ipò ẹni àá fojú tẹ́ńbẹ́lú (ìjọmples Complex).àwọn ìtọ́kasí Adler, A..
wikipedia
yo
Journal of Community and Applied Social Psychology, 18, 96-107.
wikipedia
yo
Contemporary perÈrè on Sychotherapy and Homoxolókùnyíyà..
wikipedia
yo
The Canadian Journal of adlerian psychology, 37(1), 3–16.
wikipedia
yo
witness and victim of the Apocalypse, chapter 13 page 12 and Chapter 14 page 6.
wikipedia
yo
Díẹ̀ lára àwọn ilé tí ó ya ní harewood House, York; Oley Park, kedleston Hall, Derby.[re; Luton hòo, bedfor1979 àti Kenwood.ìgbésíayé..
wikipedia
yo
Òun ni ó jẹ́ president ilẹ̀ Amẹ́ríkà lẹ́yìn Washington..
wikipedia
yo
Oun ni o kókó lo se Ambassador ilẹ̀ oní-Republic tuntun yìí ni ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì.Ìtọ́kasí àwon Ọjọ́ìbí ní 1735Àwọn Ọjọ́aláìsí ni 1826àwọn ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Òun ati lẹverkáwọn, dominomer ọmọ ilẹ̀ Faranse kan ni wọ́n jọ gba ògo ṣíṣe àwárí Neptune ní 1846..
wikipedia
yo
Ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni wọ́n ṣe iṣẹ́ tí wọ́n gba ògo rẹ̀ yìí.ìgbésíayé..
wikipedia
yo
Olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà ni tí ó ń fẹ́ kí àyípadà wà..
wikipedia
yo
Láti nǹkan bíi òyeya ni ó ti ń sọ pé ẹni tí kò bá ní aṣojú kò gbọdọ̀ san owó-orí (no Taxation without Representation)..
wikipedia
yo
Ni 1776, ó fi ọwọ́ sí ìwé òmìnira (Declaration of Independent).ìgbésíayé..
wikipedia
yo
Òun ni ọmọ ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ tí yóó lọ sí Japan..
wikipedia
yo
Shogun iẸ̀yàsu ni ìfẹ́ sí i gidi ni, nitori ìdí eyi, wọ́n fi ibi ti àwọn Gẹ̀ẹ́sì àti Dutch ti lè máà ṣòwò lélẹ̀ ní Japan..
wikipedia
yo
Òun ni ó dá UNICEF House, Chicago sílẹ̀ ní 1889.Ìtọ́kasí àwọn ará Amerikáwọn ẹlẹ́bùn Nobel fún Àláfíà..
wikipedia
yo
Joseph Addison jẹ́ Olùkọ̀wé ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sìWọ́n bi Addison ní 1672..
wikipedia
yo
Ó kópa nínú ‘Oníb’ òun àti Steele ni wọ́n sì jọ dá ‘Speʹ sílẹ̀.ìgbésíayé..
wikipedia
yo
1152) jẹ́ ọ̀mọ̀wé ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì ní ọ̀rúndún 12th scholar..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ àkọ́kọ́ rẹ̀ àti fún ìyípadàèdè àwọn ìwé sáyẹ́ńsì pàtàkì ní ìwòràwọ̀, itoràwọ̀, ìmòye àti Mathimátìki Latedé Griki àti Lárúbáwá sí èdè Latin láti àtẹ̀jáde Lárúbáwá, látibẹ̀ ni wọ́n ti mú wọn wá sí àpaìwọ̀òrùn Europe..
wikipedia
yo
O keko ni Tours, o sosoko fun gba diẹ ni laon, láyin rẹ lo rinajo lo si apaguusu Italia, Syracuse ni Sicily, ati Antioch ni àsìá kékeré..
wikipedia
yo
ó jẹ́ ẹni ìgbà kanna pẹ̀lú William ara Conches, ó sì jẹ́ ẹni tó mọ́ sóde ẹ̀yẹ tó sì mọ fẹ́rẹ́ Fan.Ìtọ́kasí àwọn ìjápọ rẹ̀nmpHard Adel (Hard Kol) of Bath - Give And Take Ajá Afin of Bath Timeline from the Bath Royal Literary and Scientific institue From Froml's “Very’s difficult Natural Questions"Àwọn Ọjọ́ìbí ní Àwọn Ọdún 1080àwọn Ọjọ́ailaailasì ní Àwọn Ọdún 1150..Àwọn Ara Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Olù agunlóyè'GEO’ ni Dr Olú Olúlóyè ‘ Administrator’ sì ni..
wikipedia
yo
Wọ́n bí Dr àgùnlóyè ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1948..
wikipedia
yo
O kawe ni University of Ibadan laarin 1971 si 1974, UNversity of reading, U.K ní 1974 ati Massachusetts Institute of Technology..
wikipedia
yo
Oun ni Corps Marshall ati Chief Executive, Federal Road Safety Commission tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Òun sì ní minister of State for defence fún àwọn Navy tẹ́lẹ̀.Àwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
aluminiọmú ( ) tàbí aluminọmú (; ẹ wọ spelling lábẹ) jẹ́ àpilẹ̀ṣe kẹ́míkà kan nínú àdìpọ̀ BOron tó jẹ́ funfun bí fàdákà tó ṣe mọ́..
wikipedia
yo
aluminiọmú jẹ onídẹ to po rẹpẹtẹjulọ ninu igbẹle ayé, ati ibẹ to po rẹpẹtẹjulọ nibẹ leyin oKSIji ati silikoni..
wikipedia
yo
aluminiọmú ńdarapọmọra mọ àwọn kẹ́míkà yìókù kíákíá gidigidi nítoríẹ kò le dá wà fún ra rẹ̀ gẹgẹ bí onídẹ..
wikipedia
yo
Bíjì, a lè ri ní dídapo mọ́ oríṣiríṣi àwọn àlùmọ́nì bí 270..
wikipedia
yo
orisun aluminiọmú ni àdàlú irin omi.itọkasi àwọn Elimẹ́ńtì kẹ́míkà..
wikipedia
yo
Irin jẹ́ àdàlù ní pàtàkì jùlọ idẹ pẹ̀lú àkóónú adu lãrín 0.2 and 1.7 or 2.04% ní ìwúwosí..
wikipedia
yo
A ni o dinwojú lati ṣe àdàlù mọ idẹ ṣùgbọ́n a tún lè lo àdàlù àwọn àpilẹ̀ṣe míràn manganisi, Krọọ̀mù, Banadiọmú àti WolfRamu..
wikipedia
yo
Adu àti àwọn àpilẹ̀ṣe míràn ń ṣiṣẹ́ bí ìmùlẹ̀ ṣinṣin láti dènà ifo nínú átọ́mu ayonu.References..
wikipedia
yo
.MP is the Internet Country Code Top-Level domain (Cctld) for northern Mariana Islands..
wikipedia
yo
Inmm ni ami oro orile-ede ti ipele ti o ga julo lori ero ayelujara (Cctld) fun Burma (lònìí gegebi isokan ile).. ↑ Sta)..
wikipedia
yo
Julius Kambarage Nyerere (13 April, 1922 – 14 October, 1999) Fi igba kan jẹ́ Ààrẹ ilẹ̀ Tanzania àti ti tàngayíká tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí ara TanSaniiawọn Ààrẹ Tànsáníà..
wikipedia
yo
Botswana, Loníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Ilẹ̀ Botswana (), jẹ orílẹ̀-èdè Adémọarinlẹ̀ to bùdó sí apágugúsù Áfríkà..
wikipedia
yo