cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
ayẹyẹ ẹ̀bùn yìí jẹ́ ìkan lára àwọn ayẹyẹ ẹ̀bùn tó lókìkí jùlọ ní gbogbo àgbáyé..
wikipedia
yo
Òsì tún jẹ́ ayẹyẹ ẹ̀bùn tó pé jùlọ tí ó sì ma ń dágbéléwọ́ lórí èrò amóùnmáwòran ní orílẹ̀ èdè tó ju igba lọ..
wikipedia
yo
Awon ebun imo ijinle fiimu bi tiẹ̀ ni Grammy Awards (fun orin), Emmy Awards (Fun amóùnmáwòran), ati Tony awards (fun Tiata) awon ebun Adèmí..
wikipedia
yo
CHESTER Bomar Himes (29 July, 1909 – 12 November, 1984) jẹ́ olùkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òkọ̀wé ara Amerinsiwon omo Afrika Ame AMẸ́RÍKÀ..
wikipedia
yo
olùkọ̀wé tàbí òǹkọ̀wé ni ẹnikẹni ti ṣe iṣẹ àkọsílẹ̀...
wikipedia
yo
William Edward Burhardt du Dobo ( ; Oṣù Kejì 23, Ibra – Oṣù Kẹjọ 27, 1963) jẹ́ ará Amẹ́ríkà tó jẹ́ alákitiyan àwọn ètò aráàlú, Pan-Afrika:Ní, Onímọ̀ ọ̀rọ̀-àwùjọ, Olukọ̀wé ìtàn, Oroko, àti olóòtú..
wikipedia
yo
David Levering Lewis tó jẹ́ Olùkọ̀wé Ìtàn kòole pé, “Nígbà àjọ iṣẹ́ rẹ̀ fún ọjọ́ pípẹ́, w..
wikipedia
yo
Du pèwe gbiyanju gbogbo ojutu to se e se si iṣoro iseleSunder orundun Ogun —Igbọwọ Eko, propaganda, ilọpo, ìpinu funraeni tọmọorile-ede, awon eto o̩mo̩nìyàn, isepin asa ati okò, iselu, Irokosti Kariaye, Igbinodi-odi, ìtìlẹ́yìn orile-ede agbaye keta."du ( pari eko re ni Harvard, nibi to ti gba iwe-ẹri omowe (Ph.D) ninu itan; leyin re o di ojogbon itan ati oro-okowo ni Atlanta University..
wikipedia
yo
Ó di olórí ẹgbẹ́ ọmọorílẹ̀-èdè fún iresíwájú àwọn ènìyàn aláwọ̀ (NAACP) ní 1910, ó sì di olùdásílẹ̀ àti olóòtú ìwé-olóṣooṣù NAACP The Crisis..
wikipedia
yo
Du pèwe bọ́ sí àkíyèsí tíorílẹ̀-èdè nígbà tó tako ẹ̀rọ Booker t..
wikipedia
yo
WASHINGTON láti faramọ́ ìjítí Jim dìdi lariǹrin àwọn aláwọ̀ta àti aláwọ̀dúdú àti ìgbà àwọn fún àwọn gulọ́nù, ó Ṣakitiyan rẹ̀ fún àdùn fún Ìdá olóṣèlú fún àwọn aláwọ̀dúdú láti lẹ́ bá dájúdájú àwọn ètò Jajá, àti ìdá elite àwọn aláwọ̀dúdú tí wọn kò ṣiṣẹ́ fún ìtàn àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.Igba ewé ebi William William Burhardt du (Aki jẹ́ bíbí ní ọjọ́ 23 Oṣù Kejì ọdún kẹrin, ní Great Bardọ́gba, ní Great Bar kini ní gbogbo gbogbo Maria Ma ní Marlẹ̀ (iná.. Tuntun du ( Lé́n àti Gukúlẹ́ lẹ́ lẹ́ lẹ́ lẹ́ gbogbo ọdún Gudùn ní Ìàn Ìyàn ọdún Nàìjíríà fún àwọn aláwọ̀dúdú láti ọdún gbogbo ní àwọn ètò pẹ̀lú àwọn ẹ̀kejì àti The lẹ́ lẹ́ Nàìjíríà ní wọn ní ìpàkò ní àwọn aláwọ̀dúdú fún àwọn ìdùn àwọn ìjá ọdún Abilẹ̀ ní ọdún Áfríkà ní àwọn ìwá ní ìjí ní àwọn Jadùn lẹ́ àwọn Gudùn àti Gujá àti wọn ní àwọn ṣàfihàn ní àwọn ní àwọn ọmọ kini àwọn ewé àti Ìbàdàn fún àwọn ní àwọn bá ní ètò ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tún ní mọ́kàn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ṣàfihàn tí wọ́n ń ní ọdún ìdùn àwọn àwọn ọmọ Áfríkà, ní ìyàn ( Kan lẹ́ lẹ́ ní ọdún ìpínlẹ̀ ní ìjí àwọn ó lá ọdún aláwọ̀ta àti Great tí ètò ìdùn àwọn ní àwọn ní àwọn lé pẹ̀lú “ àwọn ìdùn oni àwọn ẹ̀kejì Gujá láti àwọn ní àwọn àwọn ètò ṣiṣẹ́ fún àwọn ìnù àwọn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ní wọn tí*
wikipedia
yo
O dagba ni Great Barrington, ilu to kun fun awon omo Anglo-Amẹrika..
wikipedia
yo
Ẹbí Mary Silvse Burhardt jẹ́ ikan lãrín àwọn olugbe Aláwọ̀dúdú Olómìnira iye díẹ̀ ni Great Barrington, nitori ilé ti wọ́n ni látọjọ́ pípẹ́ ni ìpínlẹ̀ na..
wikipedia
yo
Ẹbí wọn wá láti iran asiwaju lati Hollándì àti Afrika..
wikipedia
yo
Tom Burhardt, tó jẹ́ ẹrú tẹ́lẹ̀ (Ó jẹ́ bíbílọ́mọ ní ìwọ̀òrùn Áfríkà lãrín ọdún 17) gba òmìnira rẹ̀ nípa ìwọ̀fà (1780) Bí ajagun aláìlókun nínú ẹgbẹ́ ajagun Kaptein John SAbẹ́poor..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí Du Ganbo ṣe sọ, ọ̀pọ̀ nínú àwọn ìran aṣíwájú ìyá rẹ̀ ni wọ́n kó ipa pàtàkì nínú ìtàn agbègbè ibẹ̀.Alfred du Notibo, láti Haiti, ní ìran Huguenot láti Fránsì àti Afrika..
wikipedia
yo
Du Noti's gba ẹbun Ilẹ̀ Púpọ̀ ní Bahamas fún ìtìlẹyìn tí wọ́n fún Ọba George 3K nígbà rògbòdìyàn ìjídìde Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
On long Cay, Bahamas, James du ìsun bí àwọn ọmọ pupọ pẹlu àwọn ẹrú rẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tó darí dé New York ní 1812, James mú John àti Alexander nã wá, tí wọ́n jẹ́ méjì nínú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, láti le bá lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ní Connecticut..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí James du àkọ́sórí kú, àwọn ọmọkùnrin Aláwọ̀dúdú rẹ̀ jẹ́ kíkólọ́mọ látọ̀dọ̀ àwọn ẹbí rẹ̀ bi bẹ ó fi tipátipá fi ilé-ẹ̀kọ́ sílẹ̀ lati ṣiṣẹ́..
wikipedia
yo
Alexander di oníṣòwò ní New Haven ó sì gbé Sarah Marsh Lewis níyàwó, wọ́n sì bí ọ̀pọ̀ ọmọ..
wikipedia
yo
Lrin Ẹ̀wádún 1830 Alexander Lọ sí Haiti láti lọ gba ìjẹMògún rẹ̀..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ ni ó ti bí Alfred ọmọkùnrin rẹ̀ ní bí ọdún 1833..
wikipedia
yo
Alexander padà sí New Binven Láì mú ọmọ yí lọ́wọ́ tàbí ìyá rẹ̀ na.Awon Ìtọ́kasí àwọn ará AmeriÌyọnuwon Omo Afrika AMẸ́RÍKÀ..
wikipedia
yo
Richard Nathaniel Wright (September 4, 1908 – November 28, 1960) jẹ́ Olùkọ̀wé Ọmọ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ni 1908àwọn Ojoaláìsí ní 1960àwọn Olukọwe AraAmén Ọmọ Ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Hakeem Iguaodalo Bello Osagie lọ́yà ni, 'Petroleum Economist ni o si tun jẹ 'Financial Technonòtiyùn
wikipedia
yo
A bi i ni ọjọ Kokiandinlogbon osu keji odun 1952..
wikipedia
yo
Awon ile-eko ti o lo ni King's College, Lagos 1966-1971, Oxford University, Oxford 1973-1976, Cambridge University, Cambridge 1976-1979, Hapààlà Business School, USA 1978-1980, Nigerian Law School 1981–1982..
wikipedia
yo
Oun ni o je 'Special Assistant to the Presidential adviser on Petroleum and Energy' abẹ́ Sheu Shegari..
wikipedia
yo
Òun ni akọ̀wé Nigerian holified Natural Gas (nlng) Committee ti o ṣeto bi Nodeng project ṣe bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
Looya Udoma ati Bello Osagie ni ile-iṣẹ looya wọn...
wikipedia
yo
deltáaLebanoni North (issele Uku), Anisiseto South, Bodepo (Borna), Burútu (burutu), Ethiópíà East (Isiọkọ), Ethiópíà West (OGHO) ika North East (Owa Olububu), ika South (AGBOR), Ísókó North (Ozoro), Ísókó South (oleh), Ndokwa East (aboh), Ndokwa West (Kwale Awo-iAD), Okpe (O|keKpé), Oshimili North, OyO South, Alani (Ni) Sapele (Sapele), Udu (otor Uroko), ughhe North (ugh35), ughhe South South (Mo Town), Ukwu, Uvwi (Effets), Warri South (Warri), Warri North (koko) Warri South-West South-West
wikipedia
yo
.S is the Internet country code top-level domain (cctcld) reserved for the designation sValBard and Jan Mayen..
wikipedia
yo
currently it is not used as svalBar and Ján mayen are parts of Norway..
wikipedia
yo
Home page owners on SvalBar Have .No or .com Like in Norway..
wikipedia
yo
Abocs jẹ́ fún ọ̀pọ̀ ọdún àmìọ̀rọ̀ orílẹ̀-èdè Top-Level domain © fún Czechoslovakia..
wikipedia
yo
Ìkoko .CS wà DÓPIN díẹ̀ díẹ̀, ó sì jẹ́ píparẹ́ patapata ní January 1995.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Sikiru Àyìndé Barrister ) jẹ́ olórin Fújì ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ayinde Barrister bẹ̀rẹ̀ sí kọrin ta ní ọdún 1966- 2008, Barrister gbé àwo orin tó pọ̀ tó 127 jáde..
wikipedia
yo
Nínú wọn ní òkè àgbà (1980), Ìjọ ọlọ́mọ (1983), Nigeria (1983), Military (1984), Barry wonder (1987), Fuji garbage (1988), Music Extrava2 (1990) àti Fújì Waves (1991).Ìgbésí Ayé rea bí Sikiru Àyìndé Barrister nínú ẹbí ṣabe balógún ní ìlú Ìbàdàn, bàbá rẹ̀ ṣabe balógún jẹ́ alápatà ẹran, nígbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ oníṣòwò pẹ́pẹ́Epe..
wikipedia
yo
Ó lọ ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Muslim Mission àti ilé-ìwé Model ti Mushin tó wá nílú Èkó..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ni ó lọ sí ilé-ìwé àkọ́ṣe-Mose ti Yaba Polytechnic láti kọ nípa ìmọ̀ òǹtẹ̀wé àti àwọn iṣẹ́ ọwọ́ mìíràn..
wikipedia
yo
Àyìndé Barrister bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ láti ìgbà kékeré rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ‘ajì-sààrì’ tàbí ají-wèrè lásìkò awẹ́ àwọn mùsùlùmí; bí ó ṣe ń ṣiṣẹ́ rẹ̀ náà lọ ń kọrin pẹ̀lú rẹ̀ ..
wikipedia
yo
O sise gege bi atewe fun ile-ise ti o Pon oti Nigerian Breweries, leyin naa ni won gba gege bi Òǹtẹ̀wé ranse ni ile-iṣẹ ologun ile Naijiria Nigerian Armylatari akitiyan re, lasiko ogun abele.</>> o sise gege bi omo ogun ni eka kewaa '10th Brigade’ ti ipin keji '2nd Division' ti ile-iṣẹ ologun Naijiria labẹ ogagun ’Adeniran' o si ja fitafita ni Awka, AbaGánà ati Onitsha.Iku ati isinku ReBarrister ku ni ojo 16 Oṣu kejila 2010 ni London nibi to ti lo gba iwosan fun arun ito-suga(Diabetes)..
wikipedia
yo
Ìsìnkú rẹ̀ wáyé ní ogbó ọjọ́ oṣù kejìlá ọdún 2010 ní ilé rẹ̀ tí ó wà ní Èkó.Àwọn ìtọ́ka sí[Ìjápọ̀ Internet Superstar Ayinde Barrister dies at 62Discography of Alhaji Chief Sikiru Ayinde Barrister ìwádí lórí googleBarry Profile àwọn Ọjọ́ìbí ní 1948àwọn Ọjọ́aláìsí ní 2010àwọn akọrin Fújì ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Eko (tabi Lagos ni ede Gẹẹsi , us also ; ) ni ilu to ni ero to po julo ni orile-ede Naijiria ati ni gbogbo ile Áfríkà..
wikipedia
yo
Eko jẹ ile-aje pataki ni gbogbo Afrika ati oríta okowo ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Eko gegebi ilu-níńlá ni o ni Gdp kerin to pojulo ni Afrika, ibe si ni ebute oko-ojúomi to to bijulo ati to láápọn julo ni ile Afrika..
wikipedia
yo
Èkó ni ikan laarin àwọn ilú ti ó n ni igbẹ́dàgbà kíákíá jùlọ ni àgbáyé..
wikipedia
yo
Èkó ni orúkọ ti àwọn Yorùbá n pe ilú Erékùṣù ti ó ti di olú ilú àti ibùjókò Ijọba gbogbo-gbòò fún ilẹ̀ Nàìjíríà ni ọjọ́ òni..
wikipedia
yo
Ìlú Yorùbá ni, ṣùgbọ́n orúkọ ti àwọn ènìyàn àgbàiyé fi ń pè é ni èyí ti àwọn Òyìnbó Potogí tí ó kọ́ bẹ́ etíkun ilẹ̀ Yorùbá wò fún un..
wikipedia
yo
Oruko naa ni "Lagos", eyi ti itumo re jasi "Adágún" tabi "Osa", nitori pe Osa ni o yi ilu naa ka...Awon eya Yoruba ti Awori ni o koko tedo si agbegbe ilu Eko, labe isakoso ati ìtọ́nà olori won, Olofin, awon Awori koko tedo si Erekusu Iddo, leyin igba naa ni won bere si ni wonu awon agbegbe yoku Eko lati tedo..
wikipedia
yo
Ni sétúrì karùndínlógún {15th Century}, ìlú Èkó, bọ́ sí abẹ́ ìṣàkóso ìjọba Benin..
wikipedia
yo
Igba náà ni àwọn ológun ìlú náà sọ agbègbè ìlú náà ní Èkó, eléyìí, tí ó dásẹ̀ sí [ibi tí àwọn ológun ti ń Simi} ní èdè Edo/Benin..
wikipedia
yo
Gbogbo eléyìí ṣẹlẹ̀ lábẹ́ olórí àwọn Benin ní ìgbà náà Ọba Ọ̀rọ̀gbá..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí èyí ṣẹlẹ̀, ní ìjọba Benin fi baálẹ̀ jẹ oye, láti máa M'òjútó/ṣe àkóso, àti gbígba ìṣákọ́lẹ̀ {tribute Ìlú náà bíi agbègbè lábẹ́-fẹ̀ ìjọba ńlá ti Benin..
wikipedia
yo
Ní ọdún-un 1472, àwọn Òyìnbó Potoki{Portuguese} de sí ilé ẹ̀kọ́, àwọn Potoki náà ní Òyìnbó àkọ́kọ́, tí ó máa dé ilé -ẹ̀kọ́ láti erékùṣù orílẹ̀-èdè Europe ní ìgbà náà.Aworanítokàsí J.f..
wikipedia
yo
Odunjo (1969), ilu Eko ati Ijebu, Iṣẹ Àtúnyẹ̀wò Eko nipa Oro Agbigbaso Oju-iwe 49-54, Eko ijinlẹ Yoruba _*, fun awon ile eko giga, Apa keji, Long of Nigeria.Ìtọ́kasí are awon ile isimi tówà Ladita Hote)..
wikipedia
yo
Àwọn Ìlú ati Abúlé ní Ìpínlẹ̀ Èkóàwọn Ìlú ati Abúlé ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
|||}awon agbegbe ijoba ibile Naijiria 744 ni o wa ni Naijiriaatoitọkasi awon ipinbee ile Naijiria..
wikipedia
yo
Báhai ẹ̀sìn kan tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 1863 tí o ń mú gbogbo èyí tí ó dára lára ẹ̀sìn mìíràn lọ tí o sì ń mú kí gbogbo àwọn ènìyàn ayé para pọ̀..
wikipedia
yo
Awon ti o n sin esin yii ni won n pe ni Bahais.itọkasi esin..
wikipedia
yo
Láti oṣù karùn-ún ọdún 1975 ni ó ti di ara Grapààlàan..
wikipedia
yo
Aberdeen antigus ni wọ́n máa ń pe orúkọ àgùntàn kan tí ó gbajúmọ̀ ní Aberdeen..
wikipedia
yo
Àwọn ará ìlú Aberdeen ni wọ́n ń pè ní Aberdonian.Europe..
wikipedia
yo
Agbegbe kan ni ila-oorun Scotland ni Aberdeenshire..
wikipedia
yo
Ni apa ila-oorun aberden, ise agbe ni o je won logun..
wikipedia
yo
BuChan ness ti o wa ni Aberdeenshire ni ilu ti o kangun ju ni ila-oorun ile Scotland..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú tí ó ṣe pàtàkì ní Aberdeenshire ní Aberdeen, Peterhead, FraserMíṣọ́nnárì, Inverturierie, Bella àti hun?’..
wikipedia
yo
Wọ́n dá ilé-iṣẹ́ ẹja sílẹ̀ ní Aberdeen, Fraserpó! àti Peterhead..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn tí ó wà ní agbègbè yìí ní 1961 jẹ́ Aráú, 503...
wikipedia
yo
máì márùn-ún ní ìlú yìí sì mọ̀nmouth, ní apá ìwọ̀-oòrùn..
wikipedia
yo
Sani Abacha (20 September 1943 – 8 June 1998) jẹ́ Ọ̀gágun Ilé-iṣẹ́ Ológun Ilẹ̀ Nàìjíríà àti Olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ọjọ́ 17 Oṣù Kọkànlá ọdún 1993 títí dé ọjọ́ 8 Oṣù Kẹfà 0dun 1998 tó kú lójijì.Ìgbé ayé rẹ̀wọ́n bí Abacha ní ìlú Kano ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Nigeria military Training College ti ìlú Kaduna Ọgbà ipò Ìgbìmọ̀ in ọdún 1963 lẹ́yìn tí ó dé láti iké ẹ̀kọ́ tó çti ní ìlú Aldershot ní England.Ìgbà ikú rẹni ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹfà ní ọdún 1998,Abacha kú sí aṣọ Rock tí àwọn Ààrẹ ní ìlú Àbújá.Wọ́n sìn Abacha ní Ìlá náà ti Mùsùlùmí..
wikipedia
yo
Awon kan ni kejidinlogbon le ni paapaa, awon kan ni awon apa yan ni won paa, ati bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lo ni pato Kosi eni ti o mo idi iku re.leyin iku re, won fi Ogbeni AbdulSalami Abubakar se olu dari ti ipinle ni osu kewa odun 1998.Awon itọkasi awon aare ile Naijirimeje ogagun ara Naijirimeje oga ọmọṣẹ́ Agbógun Naijiria..
wikipedia
yo
Abdullámì Abubakar (ọjọ́ìbí June 13, 1942) jẹ́ ọmọ ológun ará ilẹ̀ Nàìjíríà àti olórí ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà láti ọjọ́ 9 Oṣù 6, 1998 títí di ọjọ́ 29, osù 5, 1999 lẹ́yìn ìgbà tí Sani Abacha Kú.Ìtọ́kasí Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
.ff je ami orile-ede Top-Level domain fun Internet © ti Ile Central African Republic..
wikipedia
yo
O Pala pẹlu Okun Pàsífíìkì, o wa ni Ilaorun Okun Japan, ṢÁÍNÀ, Ariwa Korea, Guusu Korea ati Rọ́ṣíà, o gun lati Okun Okhotsk ni ariwa de Okun Ilaorun Ṣáínà ati Taiwan ni guusu..
wikipedia
yo
Àwọn lẹ́tà tí wọ́n fi ń kọ orúkọ Japan túmọ̀ sí “orísun ọrun”, èyí ló jẹ́ ìdíẹ̀ tí a fi ń pe Japan ní “Ilẹ̀ Ìlàdìde ọrun”.Japan jẹ́ Arkiọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ àwọn Erékùṣù 6,852..
wikipedia
yo
Àwọn Erékùsù ibẹ̀ tí ó tóbi jùlọ ní Honshu, jíjí, Kyushu àti Shikokú, tí àpapọ̀ wọn jẹ́ èdè mẹtadínrún (97 ìdùn ìdun ilẹ̀ Japan..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn erékùṣù wọnyi jẹ́ olókè, opó jẹ́ Oniẹlẹ́rù; fún apẹ̀rẹ̀, ibi gígajùlọ ní Japan, Òkè Fújì, jẹ́ Oniẹlẹ́rù..
wikipedia
yo
Japan jẹ́ orílẹ̀-èdè Oríwa tó iye àwọn ènìyàjùlọ, pẹ̀lú àwọn ènìyàn tí wọ́n tó ẹgbẹgbẹ̀rún 128..
wikipedia
yo
Agbegbe títóbiju Tokyo, to ni oluilu de facto Tokyo ati àwọn ibile ayika re, ni ó jẹ́ agbègbè Metgbòde títóbijùlọ lágbàyé pẹ̀lú iye ènìyàn tó tó ẹgbẹgbẹ̀rún 30.iwadi iseọ̀rọ̀ijọ́un fihàn pe awon ènìyàn ti dójú ní Japan láti ìgbà tó ya bí igba òkútaijọ́un oke..
wikipedia
yo
Ìgbà àkọ́kọ́ tí a kò gbọ́ nípa orúkọ Japan nínu ìwé àkòré jẹ́ nínú àwọn ìwé ìtàn Ṣáínà láti Ọ̀rúndún Miper sk..
wikipedia
yo
Ipa látọ̀dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè míràn jẹ́ títẹ̀lé pẹ̀lú idagbe ìgbà pípẹ́ bó ṣe hàn gbangba nínú ìtàn Japan..
wikipedia
yo
Ní ìgbẹ̀yìn ọ̀rúndún 19K àti 20K ìjàbori nínú Ogun Ṣáínà àti Japan Àkọ́kọ́, Ògùn Rọ́ṣíà Japan, àti Ogun Àgbáyé Mihamu gba Japan láyè láti fẹ́ ilé rẹ̀ nígbà itoja ogun..
wikipedia
yo
Ogun Ṣáínà àti Japan Kejì ọdún 1937 tan títí dé Ogun Àgbáyé 2K, tó wá sópin ní 1945 lẹ́yìn ijùbombu Fítọ́mu sí Hiroshima àti Nagasaki..
wikipedia
yo
Láti ìgbà àjájì alátíjá rẹ̀ ní 1947, Japan ti di ọba oníkòkò ìrúkò pẹ̀lú òkò ìtì ìkò kò ní gbígbé.Alágbára Idáó ní Japan, Japan ní ó ní ìdá ní órún fún òdálànà àti àti gẹ́gẹ́bí Agbara Àga wá́nnù..
wikipedia
yo
Bakanna o tun je atajalode kerin titobijulo ati Arajalátòde Kẹrin Títóbijulo lagbaye..
wikipedia
yo
Bótilẹ̀jẹ́pé Japan lóníbiṣẹ́ ti jọ̀wọ́ ẹ̀tọ́ rẹ̀ láti gbé ogun, ó di ilé-iṣẹ́ ológun òdeòní mú fún abo àti iṣẹ́ àlãfíà..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn Singapore, Japan ló ní ìpànìyàn tó kéréjùlọ lagbaye..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́bí un àti WHO ṣe díye, Japan ló ní ìrètí ìgbéayé gígùnjùlọ lãrín gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè lágbàùn..
wikipedia
yo
Bakanna o tun ni iku ọmọ-owo Tokerejulọ kẹta, gegebi un se so.itọkasi..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ará ilẹ̀ Ṣáínà jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Orílẹ̀ Àsíá.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Awon wonyi ni àkójọ awon oluilu awon ipinle Naijiria.Wo eleyi naoluilu ipinle Naijiriàwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Ikeja je oluilu ipinle Eko ni guusu iwo oorun Naijiria ..
wikipedia
yo
Awon olugbe rẹ, ni asiko ikaniyan odun 2006 je 313,196..
wikipedia
yo
Pápá Ọkọ̀ Òfurufú ti Murtala Muhammed wà ní ìlú náà..
wikipedia
yo
Ikeja ilu ti Femi Kuti ti wa, ti o si je ilu iya Lagbaja..
wikipedia
yo
Ile ise radio bii Eko FM ati Radio Lagos wa ni ilu Ikeja.itan ilu yi Ikeja, eyi ti won n pe ni "Akeja" tele, je ilu ti won fi oruko re le latari orisa awon Awori ti ilu Ota.Awon itọkasi oluilu ipinle Naijiria..
wikipedia
yo