cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ìyàtọ̀ wọn kedere sí àwọn kòkòrò míràn ní eṣinṣin ní ìyẹ́ ìwa méjì ní Aya-arin àti Pair of Haltere meji, tó wá láti ìyẹ́ ẹ̀yìn, ní Aya-Ìkẹyìn.. | wikipedia | yo |
(Àwọn irúẹ̀dá eṣinṣin kan yàtọ̀ nítorípé wọn kò le fọ́).. | wikipedia | yo |
Àwọn kòkòrò míràn tí wọ́n tún ní ìyẹ́ tó únṣíṣẹ́ àti irú Halteres kan ní strepsivra, wọ́n sì yàtọ̀ sí àwọn eṣinṣin nítorípé àwọn strejavtein ní Halteres wọ́n ní Aya-ãrín àti iye Olùgbàlà wọn ní Aya-ìkẹyìn.. | wikipedia | yo |
Esin The Horse (equus Feade Caballus) is a domesticated, Oddd-ed, HooFed Mammal.. | wikipedia | yo |
It belongs to the taxonomic family equidae and is one of two extant subspecies of equus Fago.. | wikipedia | yo |
The horse has eVolved over the past 45 to 55 million years from a small multi-toed kúnú, eopus, into the large, single-toed animal of today.. | wikipedia | yo |
Inroko began Domeating Horses Around 4000 BC, and their domestication is believed to have been widespread by 3000 BC.. | wikipedia | yo |
Horses in the subspecies Caballus are domesticated, although some domesticated populations live in the wild as feral Horses.. | wikipedia | yo |
These fẹ́ral populations are not true Wild Horses, as this term is used to describe Horses that have never been domesticated.. | wikipedia | yo |
There is an extensive, Kirialized vo5BFR5BFR used to describe equine-related Concepts, Ogúnd everything from Anatomy to life stages, size, Colors, MarKings, Betods, Absalomution, and behavior.Horses are 26Iyawo to run, allowing them to quickly escape predators, rẹwàsing an excellent sense of Balance and a strong fight-or-flight response.. | wikipedia | yo |
Female Horses, called Mares, carry their young for approximately 11 months, and a young horse, called a fọ́al, can stand and run shortly following birth.. | wikipedia | yo |
Most látòkècated Horses Beat Training Under a RES or in a harness Between the Ages of Two and Four.. | wikipedia | yo |
They reach full adult development by age five, and have an average lifepanpan of between 25 and 30 years.Itọ̀ iléàwọn àmì-ìdámọ̀ tẹ́júan ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
UYÓ ní Olù-Ìlú Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní gúúsù Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
UYÓ di olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní ọjọ́ ketalelogun Oṣù Keta(Sept 23), ọdún 1987 nígbà tí Akwa Ibom yapa kúrò lára Ìpínlẹ̀ Cross River.. | wikipedia | yo |
Gẹgẹ bi abajade eto ikaniyan Naijiria odun 2006, iye awon eniyan ti o n gbe Uyo (ati ni ilu Itu) je 427,873àwọn itọkasi ipinle ipinle Naijiria.. | wikipedia | yo |
Òṣogbo jẹ́ ilú nlá kan ni ipilẹ Osun ni orile-ede Naijiria, bakan naa ni o jẹ́ olú ìlú fun ipinlẹ naa ni apa iwo oorun ile Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ogbeni Gboye oyetola ni Gomina Ipinle Osun lọwọlọwọ.. | wikipedia | yo |
Òṣogbo di olú ilú fún ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ni ọdún 1991.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni ó tún jẹ́ olú ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ fún ìlú Òṣogbo, tí ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ náà sì wà ni òkè Baálẹ̀, nígbà tí ìjọba ìbílẹ̀ Ọlọ́rundá ń ṣojú agbègbè idúndún nílù Òṣogbo.Àwọn ìtọ́ka sí ìpínlẹ̀ Osunìlú ìpínlẹ̀ Nàìjíríàgbèwọ̀ ilú àti Abúlé ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.. | wikipedia | yo |
Paul Kagame ( ; Ọjọ́ìbí 23 October 1957) Lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ilé Rùwáńdà Ìkẹfà.Ìtọ́kasí Ààrẹ Ilẹ̀ Ruwandáàwọn Ara Rùwáńdà.. | wikipedia | yo |
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ilẹ̀ Rwanda jẹ́ orílẹ̀-èdè ní apá ìlàoòrùn Afrika.Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Kìgálì jẹ́ oluilu orile-ede Rwandaji Rwandáàwọn oluilu ni Afrika.. | wikipedia | yo |
BÙRÚŃDÌ (Pípè ), Loníbiṣẹ́ bí Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Ilẹ̀ Burundi (, ; , ), jẹ́ orílẹ̀-èdè Adétúnsãrin ní agbègbè àwọn Adágún níńlá ní apáÌláỌ̀run Áfríkà tó ní bodè mọ́ Rwanda ní àríwá, Tanzania ní Ilaorun àti Gúúsù, àti Orílẹ̀-èdè Olómìnira Olóṣèlú Ilẹ̀ Kóńgò ní ìwọ̀òrùn.. | wikipedia | yo |
Bótilẹ̀jẹ́pé orílẹ̀-èdè nã jẹ́ Adétúnsãrin, ọ̀pọ̀ bodè rẹ̀ ní apá gúúsùìwọ̀ wà níwájú Adágún Tanganyika.Àwọn Ọ̀wá, Tutsi, àti Hutu ni wọ́n ti dójú ní Burundi látìgbà tí orílẹ̀-èdè nã ti jẹ́ dídásilẹ̀ ní ọ̀rúndún márùn sẹ́yìn.. | wikipedia | yo |
Burundi jẹ́ jíjọba lélórí bí Ilẹ̀ọba látọwọ́ àwọn Tutsi fún ọgọ̣́rún méjì ọdún.. | wikipedia | yo |
Ṣugbọn látìbẹ̀rẹ̀ orundun ogun Jemani ati Belgium gba ori ibẹ̀ wọ́n sì sọ ibẹ̀ di ileàmúsìn to ruko rẹ̀ únjẹ Ruji-Uclusi.Ballt ati baba ni meji ninu àwọn ohun àlúmọ́nì ti Burundi ni.. | wikipedia | yo |
Bakanna Burundi únta kọfí ati ṣúgà.Àwọn Ìpínlẹ̀ Ijọba Burundi jẹ́ pipin si igberiko 18, 117 Communes, and 2,638 Collines (Hills).. | wikipedia | yo |
Prorati _ are strucbọ́gbọ́n upon these boundaries.. | wikipedia | yo |
In 2000, the Province encom bujumbura was compassionted into two provincesces, bujumbura rural and bujumbura mairie.. | wikipedia | yo |
The ọpast Province, rumon, was created on 26 March 2015 from portions of bujumbura rural and bururi.itọkasi.. | wikipedia | yo |
Ẹgbẹ́ ìgbéru Action Group jẹ́ ìkan nínú àwọn laami-laaka ẹgbẹ́ òṣèlú ẹfi ominira pọ̀ fún orile-ede Naijiria ti won da sile ni ìlú Ibadan ń inú oṣù kẹta ọdún 1951 lati ọwọ́ ìlọ Obafemi Awolowo Adesele idi ti won fi dá ẹgbẹ́ yi sílẹ̀ ni lati ru ìmọ̀sílara awon omo omo orile-ede Naijiria lati gbe igbese ati darapọ̀ mọ́ àwọn ẹgbẹ́ ìgbe ìkan gba ominira, ati lati da ẹgbẹ́ iselu nlo lọ́wọ́ ko paa paa jùlọ ni apá ìwò-oòrùn orílẹ̀-èdè Naijiria.. | wikipedia | yo |
Àwọn ikọ̀ tí wọ́n jẹ́ àpapọ̀ ẹgbẹ́ ọmọ Odùduwà ti alàgbà Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ dá sílẹ̀ nígbà tí ó wà ní London gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́.Ìtàn ẹgbẹ́ òṣèlú náání ọdún 1941, Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ bẹ̀rẹ̀ ẹgbẹ́ Nigerian Youth Movement ní ìlú Ìbàdàn láti má kọ́ àwọn ọ̀tọ̀kùlú ìlú tí ó kàwé.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1945, Awólọ́wọ̀ tún dá ẹgbẹ́ ọmọ Odùduwà sílẹ̀ láti mú kí Ykúnpọ̀ wà lãrín Yorùbá.Wọ́n ní ẹgbẹ́ náà jí ṣe ẹgbẹ́ òṣèlú ṣùgbọ́n ó wà fún tọkùnrin tobìnrin ilẹ̀ Yorùbá láti mú ìdàgbàsókè bá Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Ọpọlọpọ eniyan ni iwọ-oorun Naijiria lo se atilẹyin fun ẹgbẹ naa.Ni March 21, ọdun 1951, Oloye Obafemi Awolowo da egbe Action Group kale ni iluIbadan.. | wikipedia | yo |
Ní oṣù kẹrin ọdún 1951, olóyè Samuel Akínsànyà mú àbá wá pé kí wọ́n pe àwọn ọ̀tọ̀kùlú ènìyàn ní ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà láti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú náà.. | wikipedia | yo |
Ọpọlọpọ Oriwa Oloye ni o kopa ninu ipade ti o waye ni Ibadan ni Oṣu Kẹwa dun 1951, lati da ẹgbẹ oṣelu naa kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé Dokita eléré Akinola Maja tí ó dari ipadé náà kí iṣẹ́ Olóè.Awon Itọ́ka sí ̀wọ́ sí ìṣẹ sí oníwo elé nínú gbà sí gbà • ogun ní ọdún kan sí pẹ̀lú pẹ̀lú kan sí pé olé nì sí ọdún ti o risi * * sí * kan * pé elé iriń tí ó ja tí ó yẹ olè pàru elé ti o ja * * | wikipedia | yo |
Béwéṣe | wikipedia | yo |
Chima nwafor (Aláìsí 25 March, 2005) je oloselu omo ile Naijiria ati igbakeji gomina ipinle Abia si Orji Kalu.. | wikipedia | yo |
Ó kú ní March 21 2005 wọ́n sì sin ín ní September 2 2006 ní Uulu rẹ̀ ní Umuma ní Ìpínlẹ̀ Anambra.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣe isn ìdágbére fún un ní St Clement's Anglican Church, Umuójìma ni osiṣioma ńwá local government ní ìpínlẹ̀ Anambra.. | wikipedia | yo |
ÀLÙFÁÀ tí ó ṣe isn fún un ní UgoChuch Ezeokeoke.Ìtọ́kasí ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Christopher Adebayo Àlàó àkàlà ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹfà ọdún 1950, ó sì kú ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kínní ọdún 2022 (1950 – 2022).. | wikipedia | yo |
Christopher Adebayo Àlàó àkàlà jẹ́ olóṣèlú àti gómìnà nígbà kan rí ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2019, ó díje dupò Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo lẹ́ẹ̀kan sí lálà ẹgbẹ́-òṣèlú Action Democratic Party(ADP) ṣùgbọ́n ó yára dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ All Progressive Party(APC) kí ìdìbò ó tó wáyé.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyoàwọn ọmọ Ògbómọ̀sọ́.. | wikipedia | yo |
O jẹ oloselu ara ile Naijiria ati Gomina Ipinle Abia lati odun 2007 titi de 2015.. | wikipedia | yo |
Ni igba ri o jẹ oṣiṣẹ ijọba ati pe o jẹ olori awọn oṣiṣẹ ijọba ni abẹ́ Gomina Orji Uzor Kalu.. | wikipedia | yo |
O jẹ ọmọ ẹgbẹ oselu PDP, lọwọlọwọ.Awon itọkasiawon Gomina Ipinle Abia.. | wikipedia | yo |
Robert Gordon Menzies jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Australia ní Menzies.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ olóòtú ìjọba ilẹ̀ Australia fún ọdún mọ́kàndínlógún.. | wikipedia | yo |
Ni aarin 1928 si 1934, o wa ni Victoria State legislature.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó ṣe, ó wọ Federal House of Representative.. | wikipedia | yo |
O di Attorney General Ile Australia ni aarin 1935 si 1939.. | wikipedia | yo |
O fi ori oye sile fúnraàrẹ ni 1966.itọkasi awọn ara Australia.. | wikipedia | yo |
Olúṣẹ́gun kòkúmọ́ àgagu (born 16 February 1948) jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti gómìnà ìpínlẹ̀ Òndó láti 29 May, 2003 títí di 23 February, 2009 nígbàtí ilé-ẹjọ́ Alátùnda ní ìlú Benin fagilé ìdìbòyan April 2007 nítorí pé kò bọ́ fìn mú.Wọ́n bí i ní FerbPúpọ̀ 16, 1948 ni Okitipupa; Òndó State.. | wikipedia | yo |
O bẹrẹ ile-ẹkọ ni St Luke's Anglican School, òkiti pupa ni 1954.. | wikipedia | yo |
Ó tún lọ sí Ebenezer Methodist School, Òkè-Adó, Ìbàdàn ni 1958.. | wikipedia | yo |
Ó tún lọ sí Baptist PriCY School, Sabon-GARIO, Kano.. | wikipedia | yo |
O wa pari Eko Primary School re ni Ebenezer African Church School, Ibadan.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, ó lọ sí University Ìbàdàn láti ka Botany.. | wikipedia | yo |
Torí pé ó mọ gẹ́ology dáadáa, wọ́n fún un ní ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ Gulf oil láti ka Geology lẹ́yìn ọdún kìíní.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní University, ó bá GuIf Oil ṣiṣẹ́ fún ọdún méjì kí ó tó wá gbse sí University of Ìbàdàn gẹ́gẹ́ bí Assistant Lecturer ní 1972.. | wikipedia | yo |
Ó lọ kàwé fún oyè Master rẹ̀ ní University of Texas láàrín 1973 sí 1974.. | wikipedia | yo |
O gba PhD ni Petroleum Gology ni ni University of Ibadan ni 1978.. | wikipedia | yo |
Kò pẹ́ lẹ́yìn èyí, ó di igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Òndó.. | wikipedia | yo |
O si ti bẹrẹ si i ṣe Gomina Ipinle Ondo lati 2003 titi di igba ti a n kọwe yọi ni 2008.itọkasiàwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Ondo.. | wikipedia | yo |
MississippiÌpínlẹ̀ kan ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà ni ó ń jẹ́ Mississippi.. | wikipedia | yo |
O duro ti awon confederate ninu Ioja abele ilẹ̀ Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Tí a bá pa ọ̀dọ́ yìí àti Missouri pọ̀, àwọn ni ó gùn jù ní gbogbo ayé.. | wikipedia | yo |
Ọdún 1541 ni wọ́n ṣe àwárí Mississippi ní Memphis, Tennessee.. | wikipedia | yo |
Ọmọ ilẹ̀ Panyan-an ti o ṣe àwárí rẹ ni wọ́n n pe ní HerNANdo dé àtọ̀.Ìtọ́kasí àwọn ìpínlẹ̀ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Àárín gbùngbùn ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Amẹ́ríkà ni ìpínlẹ̀ yìí wà... | wikipedia | yo |
Àpapọ̀ omi Missouri yìí àti Mississippi ní odò tí ó gùn jù ní àgbáyé.. | wikipedia | yo |
Louis àti KaSas City ní àwọn ìlú tí o tobi jù níbẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn ilẹ̀ Amẹ́ríkà gbà á ní 1803 ó sì di ìpínlẹ̀ ní jáwọ́n.. | wikipedia | yo |
Nínú ogun Abel ilẹ̀ Amẹ́ríkà, àwọn Union ní Missouri jà fún.Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ìpínlẹ̀ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Àṣálẹ́ Mojave California ní àṣálẹ yìí wà ní ìwọ̀-oòrùn Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Àwọn nǹkan tí ó wà ní aṣálẹ̀ yìí ní yanrìn, òkúta, volcanic Rock àti àwọn adágún odò (Lake) tí ó ti gbẹ.. | wikipedia | yo |
Lóòótọ́, wọn kò lè dákọ ní Mojave Desert, wọ́n máa ń rí àwọn ohun lọ́dún-ọnnì ilẹ̀ bíi góòlù, sílífà àti túngs ní ibẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí àwọn aginjù.. | wikipedia | yo |
Kọfí Atta Annan ( 8 April 1938 – 18 August 2018) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Ghana tó jẹ́ diplomati tó wà ní ipò gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé àgbà keje àgbájọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-èdè láti 1 January 1997 dé 31 December 2006.. | wikipedia | yo |
Annan àti àgbájọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-èdè jọ gba Ẹ̀bùn Nobel fún Àlãfíà ní 2001.Ìtọ́kasí àwọn ẹlẹ́bùn Nobel ará Ghanawọn ẹlẹ́bùn Nobel fún Àlãfíà.. | wikipedia | yo |
Blu-Ray nígi (Blu-Ray tàbí BG) jẹ́ akaaba Olójúina-ìwa amóùnmáwòrán (FM- media Storage) 15 The (tative Blu-Ray Bence (Bb) FAQ by Hugh Bennett.. | wikipedia | yo |
Oun ni o mu tábà wá si ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ti o si mu 'tatá' wá sí Ireland.. | wikipedia | yo |
Oun ati sir Humphrey Gilbert (ti o je half-brother) ni won jo ja ni ilẹ Amerika.. | wikipedia | yo |
Ìwé History of the World tí ó kọ kọ parí rẹ̀ títí tí ó fi kú.. | wikipedia | yo |
Ekuoríṣìí meji ló wà, dudu ati pupa rẹ́súrẹ́sú (brown).. | wikipedia | yo |
Àwọn eku máa ń gùn ní ìwọ̀n ínsí mẹrindinlogun ninu èyí tí ínṣì mẹjọ rẹ̀ máa ń jẹ́ ìrù.. | wikipedia | yo |
Wọ́n maa ń ba nǹkán jẹ́ púpọ̀ ni pàtàki àwọn ti o dúdú.. | wikipedia | yo |
Ní làbọ̀reti, wọ́n máa ń sin àwọn eku funfun kan tí wọ́n fi máa ń ṣe ìwádìí... | wikipedia | yo |
Àwọn Ìpínlẹ̀ Mẹ́síkò Aṣọ̀kan (Estaos unidos Mexicanos lédè Sípéènì) ,tàbí Mẹ́síkò ní Ṣókí, jẹ́ Orílẹ̀-èdè ní apá Àríwá Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ọ̀pọ̀ àwọn Mestizo wà nínú àwọn ènìyàn tó wà ní Mẹ́síkò, ìyẹn ní àwọn tí òbí wọn jẹ́ apá kan ìjíran àti apá kan ọmọ ìlẹ̀sí Mẹ́síkò.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1821 orílẹ̀-èdè yìí gba òmìnira lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjà àti ogun.. | wikipedia | yo |
Michigan jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ìpínlẹ̀ tí ó lọ́rọ̀ jù ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà ní Michigan.. | wikipedia | yo |
wọ́n ń ṣe káà púpọ̀ ní ìpínlẹ̀ yìí nítorí pé wọ́n ní ìrìn.. | wikipedia | yo |
Píkò jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú pàtàkì tí wọ́n ti ń ṣe káà ní Michigan.. | wikipedia | yo |
Àwọn ará ilẹ̀ Faransé ni ó kọ́kọ́ tẹ Michigan dó ní nǹkan bíi 1600.. | wikipedia | yo |
Michigan di Ìpínlẹ̀ kẹrìndínlọ́gbọ̀n ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà ní 1837.Ìtọ́kasí àwọn ìpínlẹ̀ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
.VV ni ami orilẹ-ede ti Top-Level domain lori Internet © fun British Virgin Islands.. | wikipedia | yo |
Awon ebun ADemi tabi ebun Oska je ebun imo ijinle fiimu ti American Academy of motion Picture Arts and Sciences ma n fun oludari ere, osere ati olùkọ̀tàn fun ise takuntakun ni ile ise fiimu.. | wikipedia | yo |