cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní apá àríwá àwọn èdè bí Bariba àti fúlà gbajúmọ̀.Àwọn ẹ̀yà ènìyàn 99% jẹ́ àwọn ọmọ Áfríkà (Yoruba, Fon, Aja, Bariba at.bb.Lo), àwọn ọmọ Europe kò ju 10,000 lọ.ìlera àti ìtọ́jú ní àrin ẹ̀wàọdún '80, àwọn ọmọ ilẹ̀ Benin tí wọ́n lè gba ìtọ́jú ìlera tó yéké dín ní 30% iyearabùdó, nítorí èyí Benin ni Òfò Ọmọdé tọ̀gájùlọ ní Áfríkà..
wikipedia
yo
Leyin iweiwe Bamako iyatọ to dara ṣẹlẹ, eyi si je ki ipese ilera o wa fun opo awon iyearabùdó.ikẹkọ ikẹkọ ko pọndandan bẹ si ni ki ṣe ọfẹ..
wikipedia
yo
Bakanna àwọn ọ̀dọ́mọ pọju àwọn bìrin lọ ní ilé Èkó..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ Ọba Benin tàbí "Ilẹ̀ Ọba Edo" (1440-1897) jẹ́ ìlú Ọba Ayéijọ́un ní apá àrin iwoorun ibi tí a mọ sí Nàìjíríà loni.ìtọ́kaokoa..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ ọba Ọ̀yọ́ jẹ́ ikan pàtàkì lára ilẹ̀ Yorùbá ni apá Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀..
wikipedia
yo
Ìdàgbàsókè Ilẹ̀ Ọba Ọ̀yọ́ kò ṣe lẹ́yìn bí wọ́n ṣe ní àgékálẹ̀ òun itọ́ ìṣèjọba tó lọ́ọ̀rìn tí wọ́n fi ń tkà àti àwọn ìlú amọ̀nà tí wọ́n wà lábẹ́ ìṣàkóso wọn láyé àtijọ́..
wikipedia
yo
Bákan náà ni wọ́n ń ṣe àmúlò àwọn ìfẹsẹ̀múlẹ̀ okòwò tó múlẹ̀ ṣinṣin àti bí wọ́n ṣe ní àgbékalẹ̀ ààtò àwọn ọmọ ogun tí wọ́n lé lẹ́gbẹ̀rún lẹ́gbẹ̀rún tí wọ́n fi ń kojú ìṣòro ààbò nínú ìlú àti lẹ́yìn odi..
wikipedia
yo
Láàrín ọ̀rúndún kẹtàdínlógún sí ọ̀rúndún kejìdínlógún sẹ́yìn, ìlú Ọ̀yọ́ ni ó ní ètò ìṣèjọba tí ó dúró ṣinṣin jùlọ ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ adúláwọ̀, tí púpọ̀ àwọn ilé ọba tí wọ́n súnmọ́ wọn sì jẹ́ ilẹ̀ amọ̀nà lábẹ́ wọn látàrí ètò ìṣèjọba àti okòwò tó fi mọ́ ètò ààbò ni ó mú kí àwọn ilé ọba náà ó sá sí abẹ́ wọn fún ààbò tó péye..
wikipedia
yo
Lára àwọn ilé ọba wọ̀nyí ní Fọn, ilé Ọba Kingdom of Dahomey tí ó ti di orílẹ̀-èdè Benin loni.Ìtàn Ilẹ̀ Ọba Ọ̀yọ́àwọn Akọni ìwáṣẹ̀ìtàn Ilẹ̀ Ọba Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ láti orí olùpilẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ọ̀ranyàn tàbí Ọ̀rànmíyàn tí ó jẹ́ Bílẹ̀ Odùduwà ní (Ilé-Ifẹ̀)..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí ìtàn ti ṣe sọ, Ọ̀rànmíyàn ṣe ìpinu pẹ̀lú àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ láti kó ẹ̀gbin tí ó ta lé baba rẹ̀ tí ń ṣe Odùduwà láti ọ̀dọ̀ àwọn alámúlégbé wọn nípa kíkógun já wọn..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n ń lọ sójú ogun náà, àwọn t'ẹ̀gbọ̀n t'aburo bá ni èdè aiyé-èdè láàrin ara wọn ni gbogbo wọn bá fi pínyà tí wọ́n sì lọ lọ́tọ̀ọ̀tọ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ gùn ìkọ̀ọ̀kan wọn..
wikipedia
yo
Látàrí èyí, àwọn ọmọ ogun tí Ọ̀rànmíyàn ní kéré jọjọ láti tẹ̀ síwájú lórí ìpinu ọkàn rẹ̀ nípa ogun náà mọ́, fúndi èyí ni òun àti àwọn ọmọ Goun rẹ̀ bá fi rìn títí wọ́n fi dé bèbè odò Niger River tí wọ́n sì fi dé ìlú ibùsa (Ṣéràssa)..
wikipedia
yo
Ìlú yí ni àwọn aláṣẹ ibẹ̀ ti gbáà ni àlejò tí wọ́n sì rọ̀ lágbára pẹlu bí wọ́n ṣe so ẹjọ́ kan tí wọ́n fi òògùn pèsè rẹ̀ mọ̀ọ́ lọ́rùn..
wikipedia
yo
Àwọn aláṣẹ tí wọ́n gba Ọ̀rànmíyàn lálejò sì sọ fún wípé kí ó tẹ̀lé ẹjọ́ náà títí dé ibi tí ejò náà yóò dúró lo ọjọ́ méje tí yóò sì wọnú ilẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Ọ̀rànmíyàn tẹ̀lé àmọ̀ràn wọn, ibi tí ejò náà wọlẹ̀ sí, ibẹ̀ náà sì ni wọ́n tẹ ibi tí ó di ìlú Ọ̀yọ́ lọ..
wikipedia
yo
OUREgan ibi tí ejò yí wole sí ni wọ́n ń pè ní Àjàká lọni..
wikipedia
yo
Ọ̀rànmíyàn tẹ ìlú Ọ̀yọ́, òun náà sì ni ó kọ́kọ́ jẹ ọba tí wọ́n sì n pèé ní “Aláàfin Ọ̀yọ́” .Nígbà tí wọ́n ń kó Ọ̀yọ́ lọ́wọ́, àwọn ọmọ ogun bárìbá gbógun láti gba ìlú tuntun náà, àmọ́ Ọ̀ràngún Ajagunla láti ilé-ìlà tí ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n fún Ọ̀rànmíyàn ni ó kó àwọn ọmọ ogun wá láti gbèjà àbúrò rẹ̀ tí ó sì gba ìlú Ọ̀yọ́ lọ́wọ́ àwọn ọmọ ogun Bgú..
wikipedia
yo
Kò pẹ́ tí ọ̀ranyàn jagun Àjàṣẹ́ ni ìyàwó rẹ̀ tòròsì tí ó jẹ́ ọmọ ọba Nupe ti gb jẹ ìyàwó rẹ̀ bí ọmọ ọkùnrin kan tí ó sọ orúkọ rẹ̀ ní Àjùwọ́n Àjàká..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, ni tọ̀rọ̀sì tún bí ọmọ ọkùnrin míràn tí wọ́n pè ní Àràbàrà tí wọ́n ń oe ní Ṣàngó..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí ìtàn ṣe sọ, Ṣàngó jẹ́ orúkọ ti àràbàbì gbà láti ọ̀dọ̀ babba ìyá rẹ̀ tí ó túmọ̀ sí ọlọ́run ará.Ìbẹ̀rẹ̀ ọdún (13th century sí 1535)ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1300 ce (common era), ni àwọn onímọ̀ sọ wípé wọ́n dá ìlú Ọ̀yọ́ sílẹ̀.Aláàfin Menwọn Àjàká ni ó gbapò ọba lẹ́yìn Ọ̀rànmíyàn, àmọ́ wọn yóò nípò nítorí wípé Àjùwọ́n Àjàká ó fẹ́ràn àlàáfíà tí kò sì nígbàgbọ́ wípé ogun ni ó le yanjú aáwọ̀ tí ó bá ṣẹlẹ̀, àti wípé ó fàyè gba gbogbo àwọn olóyè rẹ̀ láti ṣe ohun tí ó bá wù wọ́n nínú ìlú..
wikipedia
yo
ẹni tí wọ́n fi jọba lẹ́yìn rẹ̀ ní Àjàká tí a mọ̀ sí Ṣàngó, tí àwọn ènìyàn padà sọ di òrìṣà mọ̀nà-mọ́ná lẹ́yìn ikú rẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ní Àjàká padà sórí apẹ̀rẹ̀ ọba tí òun náà sì di ArogunMasa, Arogun malelo àti arógunyọ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn Àjàká ni aláàfin kórí gorin ìtẹ́ tí ó sì jagun gba ìlú ọ̀pọ̀ ìlú tí àwọn ìlú tí ó di ìgboro Ọ̀yọ́ lónìí..
wikipedia
yo
Oyo ileOyo ile ni aarin gbùngbùn ìlú Oyo, ibè naa si ni won tun n pe ni Oyo kaIwọlé, Oyo atijọ tabi Oyo-ọrọ''' ilé tàbí ayé ti o se pataki julọ ni Oyo ni ààfin àti Ọjà-ọba..
wikipedia
yo
Wọ́n mọ odi yíká gbogbo ẹnu ìloro àti ààlà ìgboro Ọ̀yọ́ ti ẹnu àbáwọlé rẹ̀ sì jẹ́ mẹ́tàdínlógún..
wikipedia
yo
Ààfin àti Ọjà-Ọba yí ní wọ́n ń fi pàtàkì ọba Ọ̀yọ́ hàn, yálà fún ẹni tí ó jẹ́ ọmọ ìlú tàbí àlejò.Ìjà àkọ́so lùlú Ọ̀yọ́ gbani nkan bí ọdún 1535, àwọn alágbára ilẹ̀ Nupe já ìṣàkóso ìlú Ọ̀yọ́ gbà nígbà tí tsoèdè tí ó jẹ́ adarí ọmọ ogun Nupe lé Aláàfin Onígbogí àti àwọn ìjòyè rẹ̀ kúrò tí wọ́n sì sá lọ sí ilẹ̀ ọba bogu tàbí Ìbàrìbá..
wikipedia
yo
Tvede ati àwọn ọmọ ogun rẹ lo Ilu Oyo titi di ibẹrẹ orundun metadilogun.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Gíríìsì (; , Ellada, ; , Hellas, ), bákannã gẹ́gẹ́ bí Hellas àti fún ibiṣẹ́ bí Hellenikí olómìnira (ellénike DemoKratia, Ellinikí dìmọ̀Kratia, ), jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní gúúsùapailaorun Europe, ó bùdó sí apágúúsù òpin Balkan Peninsula..
wikipedia
yo
Griisi ní ilẹ̀ bodè mọ́ Albania, Olómìnira ilẹ̀ Makedonia àti Bulgaria sí Ariwa, àti Túbí sí Iilán..
wikipedia
yo
Okùn àègèàní dùbúlẹ̀ sí ìlàorun rẹ̀, the okùn Ioniani sí ìwọ̀òrùn, àti okùn Mediòkúun sí gúúsù..
wikipedia
yo
Griisi ni ó ni etíodo kẹwa Kágunjulọ ni agbaye tójẹ́ ni gigun, ti o ni ọpọlọpọ iye àwọn Erékùṣù (bi 1400, 227 ni ibi ti Aọn eniyan ngbe), ninu wọn ni Crete, Dodecanese, Cyland, ati àwọn Erékùṣù Ionioni..
wikipedia
yo
Bí ọgọrin ninu ọgọrun ilẹ̀ Griisi ni ó jẹ́ ti àwọn Òkè, ninu ibi ti Òkè Olympus ni ó gajulọ tó jẹ́ .Griisi Oni fa gbongbo de asa-ọ̀làjú Griisi Ayeijọ́un, nibi ti gbogbo eniyan gba bi ibusun asa-ọlaju àpàiwoorun..
wikipedia
yo
Nitori eyi o jẹ́ ibi ibẹrẹ Oseluaralu, imoye Apaiwoorun, awọn idije Olympiki, Litireso Apaiwoorun ati itankikọ, sayensi oloselu, àwọn ipilẹ sayensi ati Mathematiki pataki, ati Drama, ati Tradi ati awada..
wikipedia
yo
Àṣesílẹ̀ yí han gedegbe ninu àwọn ibi ọ̀ṣọ́ àgbáyé UNESCO 17 tí wọ́n wà ní Griisi.Griisi jẹ́ orílẹ̀-èdè Agbásókè tó ní Human Development Index gíga, Griisi ti jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Europe láti 1981 àti Ìṣọ̀kan Okòwò àti Owógun Europe láti 2001, náto láti 1952, àti Ilé-iṣẹ́ Òfurufú Europe láti 2005..
wikipedia
yo
Bakanna o tun je omo egbe iyawo isọdọkan awon orile-ede, Tim, ati Àgbájọ ifowosowopo OKÒWÒ ni Okun dudu..
wikipedia
yo
atẹ́nsì ni olúìlú rẹ̀; àwọn ìlú pàtàkì miran níbẹ̀ tún ni Thessaloníki, PAtra, Héraulssed ati Larissa.Àwọn perifẹ̀rí ati ibile fun àmójútó, Griisi ni Perifẹ̀rí mẹtala ti wọ́n jẹ́ pípín sí ìbílẹ̀ Mokaleladọta (FM, Singular )..
wikipedia
yo
Bakanna ni agbegbe ìdáwà kan to n je oke oke Chels (oke"), Mo Míṣọ́nnárì to ni Bode mo Perifẹ̀rí Central Macedonia.Itoka awon orile-ede Europe..
wikipedia
yo
Estonia tàbí Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Ilẹ̀ Estonia jẹ́ Orílẹ̀-Èdè ní àparirù Europe.ìtọ́ka Estonia..
wikipedia
yo
Ìgbìmọ̀ ọ̀fẹ́ oníkìkáríayé (iOC ní èdè Gẹ̀ẹ́sì dúró fún International Olympic Committee) jẹ́ ẹgbẹ́ ìkójọ tó bùdó sí Lausanne ní orílẹ̀-èdè Switzerland ti Pierre de Coubertin àti Demetrios Vikelas dásílẹ̀ ní 23 June, ọdún 1894..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ jẹ́ àwọn 205 ìgbìmọ̀ OLYkíkì ti àwọn orílẹ̀-èdèÌtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìdíje OLYkí {tàbí Olympiki} jẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré ìdárayá tí wọ́n ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ooru àti ìgbà òtútù..
wikipedia
yo
Togo tabi orile-ede Togo olominira je orile-ede ni iwoorun Afrika..
wikipedia
yo
O ni Bode Mo Ghana ni apa iwoorun, Benin ni apa ìlàoòrùn ati Burkina Faso ni ariwa.itọkasi..
wikipedia
yo
Global Positioning System (Gps) (Siste ṣiṣẹ́ipo Láyé) jẹ́ Ọnàiyatọ̀ ìka ipò ohunkohun l'ori ilẹ̀-ayé pẹ̀lú Satellite..
wikipedia
yo
Ronald Wilson Reagan (February 6, 1911 – June 5, 2004) jẹ́ Ààrẹ ogójì Orílẹ̀-èdè Ìṣọ̀kan Àwọn Ìpínlẹ̀ Ilẹ̀ Amẹ́ríkà (1981–1989) àti Gómìnà Èkétalọ́gbọ̀n Ìpínlẹ̀ Kalifóníà (1967-1975).Àwọn Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1911àwọn ọjọ́aláìsí ní 2004àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Àwọn ìpínlẹ̀ Amẹ́ríkà jẹ́ àwọn Ìpínlẹ̀ Àádọ́ta tó para pọ̀ di Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Iwe-Ofin ÌBÁGBÉPỌ̀ orile-ede Amẹrika je ofin to gajulo ni orile-ede Ipinle Iṣọ Ile Amerikajiorile-ede Amerika..
wikipedia
yo
Alábùgbé tàbí olùgbé tàbí iye olùgbé nínú ìmọ̀ àwùjọ àti ìmọ̀ Urímù jẹ́ àkójọpọ̀ àwọn ènìyàn tàbí àwọn irú ohun kan pàtó..
wikipedia
yo
Ijo Katoliki tí a tún n pe ní Ijo Àgùdà tabi Ijo Katoliki Róòmù.Ìtọ́kasí Esin Krístì..
wikipedia
yo
Along with his mentor, Socrates, and his student, Aristotle, Plato helped to lay the foundations of Western philosophy and science..
wikipedia
yo
I do not mean the systematic scheme of thought which scholars have fẹsẹ̀ted extracted from his writings..
wikipedia
yo
I Alludé to the wealth of general ideas scattered through them.Plato's Sophistication as a writer is evident in his socratic Dialogues; Thi-six Dialogues and vlogteen letters have been asCridorí to him..
wikipedia
yo
Plato's writings Have Been published in several fashions; this has led to several lọjọ́mẹyà regarding the naming and rẹ̀ncing of Plato's texts.Plato's Dialogues have been used to teach a range of ìpíntán, including philosophy, Logic, Ethics, Rhec, and mathematics.Ìtọ́kasí àwọn amòye..
wikipedia
yo
oluilu je ilu ti ijoba orile-ede kan fi se ibujoko..
wikipedia
yo
Ó tún lè túmọ̀ sí ìlú tí ó bá tóbi jù lọ, tabi tí ó ṣe pataki jù lọ ní agbègbè, orílẹ̀-èdè, tabi ìpínlẹ̀ kankan..
wikipedia
yo
Fun àpẹrẹ, àwọn Olú ilẹ̀ ti ó ṣe pàtàkì jùlọ ni aiyé jẹ́ New York, ni orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà, àti London ni orílẹ̀ èdè àwọn Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Ní ilẹ̀ Erékùṣù_{} Africa , Ìlú Èkó Lagos jẹ́ olú ìlú ìwọ̀-oòrùn Áfríkà, bẹ́ẹ̀ni Nairobi ní orílẹ̀ èdè Kẹ́nyà àti Addis Ababa ní orílẹ̀ èdè Ityopiyan, jẹ́ Olú ilẹ̀ ní apá ila-oorun, ní Gúúsù-Afrika, ìlú Johannesburg ní orílẹ̀ èdè Gúúsù Africa ní Olú ìlú-u Guusa-Afrika, àti gbogbo AFrilka pẹ̀lú, nítorí wípé ìlú Johannesbuurg ni ó ní Ìdàgbàsókè àti ìtẹ̀síwájú jùlọ ní ẹ̀yà owó ṣíṣe, Idanilaraya, Asa, Ìṣẹ̀dá ohun elo, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ní Afrika..
wikipedia
yo
Ni ariwa Afrika, Ilu Casablanca ni orile ede Morocco, Cairo ni ìjYbítí/Egypt, ati Algiers ni Algeria, jẹ olu-ilu ni ona tiwon.
wikipedia
yo
Ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ìlú Ọbẹ̀-ńlá-p ni orúkọ ẹni àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ Olùbò ní òde Ùgbò..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ pé atọmọdọmọ Sepẹluwa ti o jẹ́ Awujale ìkejìdínlógún ti ilẹ̀ Ìjẹ̀bú ní olùbákin jẹ́..
wikipedia
yo
olùbákin ati aburo rẹ ti wọn jo jẹ ọmọ baba ni wọn jọ dunpo Awujale Idínlógójìdínlógójì ti ile Ijebu leyin ti oba Morogbe, Awujale ìkejìlogoji..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀dúdújoye ní orúkọ àbúrò olùbákin tí wọ́n jọ du oyè náà..
wikipedia
yo
Yorùbá bọ̀, wọ́n ni, “Ohun gbogbo lówó orí, orí la fi ń mú ẹran láwò” Òròdúdújoyè tí ó jẹ́ àbúrò ni àwọn afọbajẹ yàn dípò olùbákin tí ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n gẹ́gẹ́ bí i Awùjalẹ̀ tuntun ti ilẹ̀ Ìjẹ̀bú..
wikipedia
yo
Bí àbúrò olùbákin ṣe gun orí oyè kò ṣàìdá họ́ùhọ́ù àti yánpọnyánrin sílẹ̀ láàárín àwọn méjèèjì..
wikipedia
yo
olùbákin gbé ẹgbẹ́ ọmọ ogun ọlọ̀tẹ̀ dìde sí àbúrò rẹ̀ pẹ̀lú èrò àti gba ìjọba padà ṣòwò araàrẹ gẹ́gẹ́ bí ẹni tí òye náà tọ́ sí..
wikipedia
yo
Àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbò, Iṣẹbo-iṣoogun, bi a ti là á rí i láyé..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ ogun ọlọ̀tẹ̀ ti olùbákin gbé dìde kò lè ṣẹ́gun tí àbúrò rẹ̀ oròdúdújoyè..
wikipedia
yo
Látàrí èyí, ó pinnu láti fi ìlú sílẹ̀ fún àbúrò rẹ̀.Kàkà kí kìnnìún ṣe akápò ẹkùn kálukú a máa dọdẹ ṣe..
wikipedia
yo
Gbogbo ìsapá àti akitiyan ọrọdúdújoyè láti tu ẹ̀gbọ́n rẹ̀ lójú já sí pàbó lẹ́yìn tí ó rò pé ó sàn kí wọ́n yanjú ọ̀ràn náà ní ìtùnbí-ìnùbí..
wikipedia
yo
Ibùdó àkọ́kọ́ tí olùbákin tẹ̀dó sí lẹ́yìn tí ó kúrò ní Ìjẹ̀bú ni wọ́n ń pè ní Éhì títí di òní yìí..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó kúrò níbẹ̀, ó forí lé ìhà ìlà-oòrùn Ùgbò, ó sì tẹ̀dó sí ibi tí wọn n pè ní ode-sepẹ̀lúwà lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n tẹ̀dó tán..
wikipedia
yo
Ọ̀gangan ibí yìí ni ọ̀kan lára àwọn ọmọ olùbákin tí a mọ̀ sí ọ̀rọ̀tó ti papòdà..
wikipedia
yo
Ó ṣeni láàánú pé ọ̀rọ̀tó kò bí ọmọ kankan sáyé kí ó tó re ibi àgbà ń rè..
wikipedia
yo
Nítorí náà Bàbá rẹ̀ pinnu láti yí orúkọ òde-ṣepẹ̀lúwa padà sí ti Ọmọ rẹ̀ tí ó kú síbẹ̀..
wikipedia
yo
Láti ìgbà náà wá ni wọ́n ti ń pe ibẹ̀ ní òde-ọ̀rọ̀tọ̀ títí ó fi di òní yìí.Olùmọdan tí òun náà jẹ́ ọmọ olùbákin ni ó ṣalápàdé ọmọbìnrin kan létí òkun níbi tí wọ́n ti lọ máa ń ṣe ohun kan tí wọ́n ń pè ní 'ìpè' lóko..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí gan-an ni ó padà wá yọrí sí bí olùbákin àti òròmakin ṣe gbà láti jọ máa ṣe Ìjọba pọ̀ ní Ùgbò níbi tí ọ̀ránmakin ti wà sáájú kí olùbákin tó dé sí agbègbè náà, gẹ́gẹ́ bí Ọ̀làjà Ùgbò..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìyàlẹ́nu fún olùmọ̀dán ọmọ olùbákin pé àwọn kan tún wà ní tòsí, ti àwọn tí ó wà ní òde-ọ̀rọ̀tọ kò mọ nípa wọn tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ọjàrù ni orúkọ ọmọbìnrin tí olùmò bá pàdé n jẹ́..
wikipedia
yo
Àwọn méjèèjì bẹ̀rẹ̀ sí yan ara àwọn lọ́rẹ̀ẹ́ ṣùgbọ́n kò sí ọmọ láti inú ìbáṣepọ̀ wọn jálẹ̀ gbogbo ọdún ti àwọn méjèèjì fi wà lórí erùpẹ̀..
wikipedia
yo
Ìbáṣepọ̀ olùdán àti Ọjàludé ni ó mú àjọṣepọ̀ tí ó wà láàárín olùbákin àti òròmakin wáyé..
wikipedia
yo
Wọ́n kó ìjọba pọ̀, nítorí pé kò fi bẹ́ẹ̀ sí èrò pupọ ní agbègbè náà nígbà yẹn..
wikipedia
yo
Nígbà tí olùbákin jẹ́ olùbọ ní òde Ùgbò, àwọn ọmọ rẹ̀ kan àti lára àwọn tí ó tẹ̀lé e wá láti ẹ̀hìn kò kúrò ní òde-ọ̀rọ̀tọ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ikú olùbákin, olùmọ̀dán ọmọ rẹ̀ ni ó jẹ́ olùbọ tẹ̀lé e..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún kọjá lẹ́yìn náà, ọ̀kan lára àwọn àtọmọdọ́mọ olùbákin tí wọ́n wà ní ọ̀rọ̀tó pinnu láti wáṣẹ́ ẹja pípa síwájú ìhà-ìlà-oòrùn òde-ọ̀rọ̀tó ìgbàyẹn, látàrí àkíyèsí rẹ̀ pé àwọn ẹyẹ ńlá-ńlá máa ti apá ìhà ibẹ̀ yẹn wá..
wikipedia
yo
A ní láti jẹ́ pé omi ńlá kan wà lápá ibẹ̀ tí ẹja pọ̀ sí, nítorí àwọn ẹyẹ máa ń dọdẹ ẹja ní irú agbègbè bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Ó kó àwọn kan mọ́ra wọn sí bẹ́ rẹ̀ ìrìn-àjò sí apá ila-oorun ode-òọrọ̀..
wikipedia
yo
Nígbẹ̀yìn wọ́n ṣàwárí omi náà tí ó kún fún ògìdìgbó ẹja ńláńlá..
wikipedia
yo
‘Agbára’ tàbí ‘Ọ̀rá’ ńlá tí àwọn ẹja wọ̀ sí yìí ni wọ́n ń pè ní “Ẹ̀bẹ̀” láàárín àwọn Ìlàjẹ ìgbà yẹn..
wikipedia
yo
Kújọ́lú tẹdótẹ̀ sí ìbí tuntun yìí tí wọ́n fi ìrísí sọ lórúkọ..
wikipedia
yo
Láti inú ‘Ẹ̀bẹ̀-ńlá’ ni ọbẹ̀-ńlá ti súyọ lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún.Bí ibùdó àwọn atọmọdọmọ olùbákin ti ń gbọ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ sí i, wọ́n yan láti fi òpin sí ìjọba alájùmọ̀ṣe tí olùbákin dá sílẹ̀ pẹ̀lú olùgbọ́, wọ́n kórajọ sí ọbẹ-ńlá, wọ́n sì sọ ibẹ̀ di ibùdó olùbọ gẹ́gẹ́ bí i ọba aládé.Ìwé tí a yẹ̀wòàgbéyẹ̀wò oríkì olùbọ ọbẹ̀-ńlá ní ilé Ìlàjẹ Apá kan nínú àṣekágbá oyè B.A (hons.) YorùbáYunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ Ilé-Ifẹ̀, Nigeria láti ọwọ́ ọwọ́yele Oyèkànmí Keen Oṣù Ọ̀pẹ, 2007Ìpínlẹ̀ Òndó..
wikipedia
yo
Abrahamu (, , , ) ni ẹni tí ó dá ilé àwọn Juu sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ó sì lọ sí Haran ní gúsù Mesotá pẹlu baba rẹ̀, iyawo rẹ̀ Sarah ati lot tó jẹ́ ‘Nephew' rẹ̀ nígbà tí ó lọ sí Kenaani, ó gbọ́ ìpè Jehovah pé ibẹ̀ ni Ilẹ̀ Ìlérí fún àwọn ènìyàn rẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó ti gbé Egypt ní àsìkò ìyàn tí òun àti Lọ́ọ̀tì sì ti pínyà ní BeẸ̀tọ́tì, ó lọ dó sí HéBrian..
wikipedia
yo
Nígbà tí Jehovah yí orúkọ rẹ̀ sí Abraham èyí tí í ṣe baba orílẹ̀ èdè púpọ̀, Jehovah ṣe ìlérí fún un pé òun yóò fún ní ọmọ tí yóò jogún rẹ̀..
wikipedia
yo
Jehovah dán an wò pé kí ó pa Isaac ọmọ rẹ̀ fún ìrúbọ..
wikipedia
yo
Bí ó ti fẹ́ẹ̀ ṣe é ni Jehovah fi ọ̀dọ́ aguntan kan rọ́pò ọmọ yìí..
wikipedia
yo
Láti ọ̀dọ̀ ìyàwó rẹ̀ ìkejì, Keturah, ó bí ọmọkùnrin mẹ́fà..
wikipedia
yo
Wọ́n sin in ↑ Ihò (CAv) Mchpelah.Ìtọ́kasí Bíbélì..
wikipedia
yo
Òkè Abu jẹ́ ibi tọ̀gájùlọ ní orí Aradepo tó wà ní ipínlẹ̀ Rajasthan ní apáòrùn India.itọkasi..
wikipedia
yo
(Ọjọ́ ìbí ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1954) jẹ́ òṣèré àti olùdarí eré ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo