cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Zamfara jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ tí ètò abo ti mẹ́hẹ ní Nàìjíríà níbi táwọn jàǹdùkú àbonbo ti ń ṣe ìkọlù sáwọn aráàlú, tí wọ́n ń fẹ́mọ wọ́n ṣòfò tí wọ́n sì tún ń jí ẹran wọn lọ..
bbc
yo
Zamfara jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ tí ètò abo ti mẹ́hẹ ní Nàìjíríà níbi táwọn jàǹdùkú Àbonbo ti ń ṣe ìkọlù sáwọn aráàlú, tí wọ́n ń fẹ́mọ wọ́n ṣòfò tí wọ́n sì tún ń jí ẹran wọn lọ.
bbc
yo
Ìjọba gbàgbọ́ pé ìgbésẹ̀ rẹ̀ yóò padà so èso rere nígbẹ̀yìn gbẹ́yín..
bbc
yo
Ìjọba gbàgbọ́ pé ìgbésẹ̀ rẹ̀ yóo pada so èso rere nígbẹ̀yìn gbẹ́yín.
bbc
yo
Oscar Hassan Idris Adekunle TODE JIRA jẹ́ àràrẹ́ nilu Abeokuta.
bbc
yo
Àrólé ni òun kò bá iṣẹ́ ọnà nílé gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ oníṣẹ́ ọnà, òun kọ́ ọ ni.
bbc
yo
Ó ní òun tún ni Ìwé Ẹ̀rí Ìmọ̀ nípa iṣẹ́ ọnà ati gbígbẹ́ igi lérè láti ilé ẹ̀kọ́ṣẹ́ Olùkọ́ni fce Òṣíẹ̀lẹ̀.
bbc
yo
Lára igi tó ní àwọn máa fi ń gbẹ igi lére ni igi àpà, igi ìrókò, igi ọmọ, dóńgóyárò àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.
bbc
yo
Abeokuta jẹ ìlú ni tí o gbajúmọ̀ nílé Yorùbá, lápá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà...
wikipedia
yo
O jẹ olu-ilu Ipinle Ogun ti o tẹ̀dó si agbegbe ti o kun fun apata nla nla..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ ni Òkè Olùmọ (Olùmọ Rock) fìkàlẹ̀ sí.Itano ṣe pàtàkì láti mọ díẹ̀ nípa ìtàn ilẹ̀ Ẹ̀gbá àti irú ènìyàn tí ń gbé ìlú Ẹ̀gbá..
wikipedia
yo
Ìdí èyí ni pé yóò jẹ́ ohun ìrànlọ́wọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan tó yẹ ní mímọ́ nínú orin ọ̀gọọ̀gọ..
wikipedia
yo
Fún ìdí pàtàkì yìí, n ó o pín àkòrí yìí sí ọ̀nà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀.Bí wọ́n ṣe tẹ ìlú Ẹ̀gbá dọpọ̀lọpọ̀ Onímọ̀ ló ti sọ nípa bí a ti ṣe tẹ ilẹ̀ Ẹ̀gbá dó, tí wọ́n sì ti gbé àbọ̀ ìwádìí wọn fún aráyé rí..
wikipedia
yo
Ara irú àwọn báyìí ni Samuel Johnson, Sabiri Bíòku, AjiSafe, Delànà àti àwọn mìíràn tó jẹ́ òpìtàn àtẹnudẹ́nu.Johnson gbà pé Ọ̀yọ́ ni àwọn Ẹ̀gbá ti wá..
wikipedia
yo
O ni awọn ẹya Egba etotò le ti orírun wọn de Oyo..
wikipedia
yo
O tun te siwaju sii pe ọmọ àlè tabi ẹru ni Egba ti ko ba ni orírun lati Oyo..
wikipedia
yo
Àwọn olóyè wọn wà lára àwọn ẹ̀ṣọ́ Aláàfin láyé àtijọ́, àtipé àwọn olóyè yìí ló sá wá sí Abẹ́òkúta lábẹ́ olórí wọn tó jẹ́ àbúrò ọba Ọ̀yọ́ nígbà náà.Lana ní tirẹ̀ ní etí Ilé-Ifẹ̀ ni àwọn Ẹ̀gbá tó kọ́kọ́ dé tẹ̀ dó sí..
wikipedia
yo
Olú ìlú wọn sì ni "Iddo" tí ô wà níbí tí Oyo wà báyìí..
wikipedia
yo
Oko ni olú ìlú wọn .Egba Ake ló dé gbẹ̀yìn.AjiSafe ní ọ̀tẹ̀ ló lé àwọn Ẹ̀gbá kúrò ní ilé- Ifẹ̀ wa Ketu..
wikipedia
yo
Láti Ketu ni wọ́n ti wá sí igbo- Ẹ̀gbá kí wọ́n tó dé Abeokuta ni 1830..
wikipedia
yo
Baburi Bíòku naa faramọ eyi.Lọ́rọ̀ kan sa, àwọn Ẹ̀gbá ti Ilé- Ifẹ̀ wá, wọ́n ní ọ̀hún í ṣe pẹ̀lú ọ̀kọ̀ adàgbà, Ketu, àti Igbo-Ẹ̀gbá.Ìtàn tún fi yẹ ní síwájú síi pe ìlú Ẹ̀gbá pọ̀ ní orílẹ̀ olúkúlùkù ló sì ń ní ọba tirẹ̀, fífò ti orílẹ̀ Ẹ̀gbá fò lọ gbé wọn dé ibi tí wọ́n wà báyìí..
wikipedia
yo
GẸ́GẸ́ BÍ ÌTÀN TI SỌ, 1821 ní ìjà tó fo gbogbo ìlú ẹ̀gbà ti ṣẹlẹ̀..
wikipedia
yo
Ohun kékeré ló dá ìjà sílẹ̀ láàárín àwọn Òwu àti àwọn Ìjẹ̀bú ní ọjà Apòmù, Ogun Ọ̀yọ́ àti ti Ifẹ̀ dà pọ̀ mọ́ ogun Ìjẹ̀bú láti bá Òwu jà..
wikipedia
yo
Àgbáríjọ ogún yìí dé ìlú àwọn Òwu ní tóòótọ́ ṣùgbọ́n àwọn Òwu le wọ́n padà títí wọ́n fi dé àárín àwọn gbágudá tó wà ní Ibadan..
wikipedia
yo
Inú àwọn gbágudá kò dùn sí èyí wón ti lérò pé ogun yóò kó àwọn Òwu..
wikipedia
yo
Èyí náà ló sì mú àwọn gbágudára tún gbárajọ láti pẹ̀lú ogun Ọ̀yọ́, Ìjẹ̀bú àti ìfẹ́ kí wọ́n lè borí ogun owú..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣẹ́gun lóòótọ́ ṣùgbọ́n Lanlẹ́yìn, àkàrà ríyìíkẹ̀ ni ọ̀rọ̀ náà dá nígbẹ̀yìn..
wikipedia
yo
Kò pè é ní Ògún Ijẹ̀bú, Ìjẹ̀ṣà, Ọ̀yọ́ àti Ifẹ̀ rí i mọ̀ pé àṣé àwọn Ẹ̀gbá kò nífẹ̀ẹ́ ara wọn, wọ́n wá bèrè múrami lẹ́kún sí àwọn Ẹ̀gbá..
wikipedia
yo
Èyí tí ó wá burú jù níbẹ̀ ni ti ikú ẹ̀gẹ́ tó jẹ́ olóye ìfẹ́ kan..
wikipedia
yo
Ladi aṣiwaju ẹgba kan lọ paa nígbà tí ń dìtẹ̀ mọ́ ọn..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n àwọn ọ̀tá kò ṣàì pa òun náà ṣán.Ọ̀tẹ̀ àti tẹ̀ǹbẹ̀lẹ̀kun tí wọ́n ń dì mọ́ àwọn Ẹ̀gbá yìí ló mú wọn pinnu láti kúrò ní ibùjókòó wọn.Àwọn babaláwo wọn gbé ọ̀pẹ̀lẹ̀ ṣánlẹ̀, wọ́n rí ọdú ọ̀funṣáá..
wikipedia
yo
Wọn Olupéẹ̀ṣọ́ lo won ppé bọ̀, won ni won yoo de Abeokuta, awon alawo funfun yoo si wa lati ba won DỌ́RẸ̀Ẹ́..
wikipedia
yo
Awon babaláwo won naa ni iroyin oso lati Ìkija ojo (a n-LA-leji- ele) ara ilugun ati Awobiyii ara irọ.1830 ṣódeke lo ṣaaju pẹlu awon Egba Ake..
wikipedia
yo
Wọn kò rántí oṣù tí wọ́n dé Abeokuta mọ́ ṣùgbọ́n àsìkò òjò ni.Nígbà tí wọ́n kọ́kọ́ dé, wọ́n dó sí itòsí olùmọ̀, olúkúlùkù ìlú ṣa ara wọn jọ, wọ́n dó kiri Ẹ̀gbá Ake, Ẹ̀gbá Òkè-ọ̀nà àti Ẹ̀gbá gbágudára ló kọ́kọ́ dé sí Abeokuta..
wikipedia
yo
Ní 1831 ni àwọn Òwu ṣẹ̀ṣẹ̀ wá bá wọn tí àwọn Ẹ̀gbá sì gbà wọ́n tọwọ́ tẹsẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn Ẹ̀gbádò tí wọ́n bá ní Ìbarà lọ sọ wọ́n ní ẹgba, ninu ọ̀rọ̀ “Ẹgbagbo” ni wọ́n sì ti fa ọ̀rọ̀ náà yọ..
wikipedia
yo
Àwọn òpìtàn ní àwọn Ẹ̀gbádò ní ń gbẹ́ ipadò nígbà tí àwọn Ẹ̀gbá ní gbé ní òkè ilẹ̀..
wikipedia
yo
Òpìtàn mìíràn tún ní ìtumọ̀ Ẹ̀gbá ní “Ẹ gbà á “ lálejò nítorí pé wọ́n gba àwọn òwú ati àwọn mìíràn tí wọn ń wá abẹ́ ààbò sá sí mọ́ra.Àwọn ẹ̀yà tó wà ní ilẹ̀ ẹ̀gbà oríṣìíríṣìí tó wà nílẹ̀ Ẹ̀gbá ló jẹ́ kí ó di ìlú ń lá, pẹlu ìjọba àkóso tó lágbára ogun ló sọ ọ́ di kékeré bó ti wàyìí..
wikipedia
yo
Ní apá àríwá, ó fẹ́ dé ọ̀dọ̀ ọba, ní gúúsù ó gba ilé dé Èbúté Mẹ́ta, lápá ìlà ìwọ̀ oòrùn (Ẹ̀gbádò)Johnson ní ìlú mẹ́tàleledẹ́gbẹ̀ta (503) ló parapọ̀ dé Abeokuta lónìí yìí.Oríṣìí mẹ́rin ni àwọn Ẹ̀gbá tó wà ní Abeokuta lónìí..
wikipedia
yo
Kò parí síbẹ̀ àwọn mìíràn tún wà tí wọ́n ti di ẹgba lónìí..
wikipedia
yo
Oríṣìíríṣìí ìlú ló tẹ̀ ẹ́ dó, ìdí nìyí tí àwọn Ẹ̀gbá tó kù ṣe ń sọ pé “Ẹ̀gbá kégbà pọ̀ Lake”
wikipedia
yo
Àwọn ìlú tó kù lábẹ́ ẹ̀gbà Ake ní ìjòkó, ìjẹun, ọba, Ilará, ìjẹmọ, itọ́kú, ìmọ̀, Ehu, Keèsì, Kenta, ìrò, Erunmi, ítorí, ìtẹ̀sí, tọ́ka, ipòró àti ìjàko.Ẹ̀gbá ọ̀kẹ́-ọ̀nà ló tẹ̀ lé ẹ̀gbà Aláké..
wikipedia
yo
Àwọn ilú tó kù lábẹ́ ẹgba Òkè –ọ̀nà ni Ejigbo, gẹ́ẹ́, Ijeja, Ọ̀dọ́, Ikẹrẹku, Erunmi, Ooyete, Erinja, Ipani àti Kúnkẹ.Egba Gbára ni oríṣìí kẹta..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú tó kù ní òwe, Ìbàdàn, ìlawọ́, iwèrè, òjé àti àwọn ìlú mọkandinlogoji (39) mìíràn.Nígbà tí ogun bẹ́ sílẹ̀ ní mẹ́sàn-án lára ìlú gbágudára sá ló fi orí balẹ̀ fún olóyóò títí di òní yìí..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú náà ni ààwẹ̀, kọ́jọ́kú àgenigé, àràn, fìdítì, abẹ́nà, Akinmóorin, ìlòraa àti ìrókò.Ẹ̀gbá òwú ní oríṣìí kẹrin, àgọ́-òwú ní olú ìlú wọn, Olówu ni ọba wọn, ìlú tó kù lábẹ́ òwú ní ẹ̀runmú, Òkolo, mọ́wọ́, àgọ́ ọba, àti Apòmù.Yàtọ̀ sí àwọn tí a sọ̀rọ̀ rẹ̀ lókè yìí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀yà mìíràn náà ló pọ̀ ní Ẹ̀gbá tí wọ́n ti di ọmọ onílẹ̀ tipẹ́..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn báyìí ni a kó lásìkò ogun tàbí kí wọ́n wá fúnra wọn nígbà tí wọ́n ń sá àsálà fún ẹ̀mí wọn, tí wọ́n sì ń wá ibi ìsádi..
wikipedia
yo
Irú àwọn báyìí ni ẹ̀gún tí wọ́n wà ní Àgọ́- Ègún, Ìjàyè- ní Àgọ́- Ìjàyè, àti àwọn ìbárapa ní ìbẹ̀rẹ̀kò àti ní àrinléṣe..
wikipedia
yo
Bákannáà ni àwọn Ẹ̀gbádò wà ní ìbára ìléwọ́, onídà àti oníkólòbó bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ti ṣáájú Ẹ̀gbá dó síbẹ̀.Ẹ̀tọ́ òṣèlú àti ọrọ̀ ajéláti ìgbà tí àwọn Ẹ̀gbá ti dó sí Abeokuta ní ètò ìṣèlú wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí yàtọ̀..
wikipedia
yo
ó di pé wọ́n ń yan ọba kan gẹ́gẹ́ bí olórí gbogbo gbọ́..
wikipedia
yo
Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ ọ̀rọ̀ kò rí bẹ́ẹ̀, kọ́lọ̀mù mumu ìyá rẹ̀ gbé ní..
wikipedia
yo
Àìrìnpọ̀ ejò ló sá ń jẹ ejò níyà.Ṣé bó bá bà síwájú, tí pamọ́lẹ̀ tẹ́ lé e, tí baba wọn òjòlá wá ń wọ́ ruru bọ̀ lẹ́yìn, kò sí baba ẹni tó jẹ́ dúró..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ “Èmi -ó-gba ìwọ -ó -gba” yìí ló jẹ́ kí àwọn alábàágbé ẹ̀gbà máa pòwe mọ́ wọn pé “Ẹ̀gbá kò lọ́lù, gbogbo wọn ló ń ṣe bí ọba” Ọba wa di púpọ̀.Ìjọba ìlú pín sí ọ̀nà bíi mẹ́rin nígbà tí ọkàn wọn balẹ̀ tán ní ibùdó titun yìí..
wikipedia
yo
Lóòtọ́, ọba ló nilẹ̀, òun ló sì ń gbọ́ ẹjọ́ tó bá tóbi jù..
wikipedia
yo
Delano ní láti ilé-Ifẹ̀ ní Ẹ̀gbá ti mú ètò Ògbógbó wa..
wikipedia
yo
Wọ́n tún un ṣe, wọ́n sì jẹ́ kí ó wúlò tóbẹ́ẹ̀ tí Ilé-Ifẹ̀ pàápàá ń gàárun wó ògbóni ẹ̀gbà.Ọ̀rọ̀ ni wọ́n ń lò láti dá sẹ̀ría fún arúfin tí ẹsẹ̀ rẹ̀ tóbi..
wikipedia
yo
Àwọn oyè tó kù tó sì ṣe pàtàkì ní àpèẹnà, àkèré, báàjìkí, Báálà, báàjìto, Ọ̀dọ̀fin àti Lisa.Àwọn olórogún tún ní àwọn ẹgbẹ́ kejì tó ń tún ìlú tò..
wikipedia
yo
Láti inú ẹgbẹ́ àárọ̀ tí okùnrin kan tí ń jẹ́ Lisabi dá ṣẹlẹ̀, ní ẹgbẹ́ olórogún ti yọ jáde..
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹtàdínlógún kẹtàdínlógún ni wọ́n ń ṣe àpéjọ wọn..
wikipedia
yo
Àwọn náà ló gba ẹgba kalẹ̀ lọ́wọ́ ìyà tí ọlọyóo ati àwọn ìlàrí rẹ̀ fi ń jẹ wọ́n..
wikipedia
yo
Ara àwọn oyè tí wọn ń jẹ ní jaguna (ajagun lójú ọ̀nà) Olùkotún (Olú tí í ko ogun ọ̀tún lójú), AkinGbógun, Òṣíẹ̀lẹ̀ àti ákílégún..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ogun ni wọ́n sì ti ṣẹ̀.Àwọn Parakoyi náà tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì tí ọ̀rọ̀ bá di ti ọrọ̀ ajé àti ìṣèlú..
wikipedia
yo
Asiwaju awon Parakoyi ni olori Parakoyi.Awon ode paapaa tun je okan ninu awon atunlùúto..
wikipedia
yo
Àwọn ni wọ́n ń ṣọ́ ọjà àti gbogbo ìlú lóru.Àwọn Olóyè òde Janjankan náà a máa bá àwọn tó wà ní Ìgbìmọ̀ Ìlú pèsè fún Àpérò Pàtàkì..
wikipedia
yo
Díẹ̀ lára oyè tí wọ́n ń jẹ ní Àṣìpa, olùọdẹ àti arọ ọdẹ.Bí ọ̀rọ̀ kan bá ń di èyí ti apá lè kó ká, ó di ọ̀dọ̀ olórí àdúgbò nì yẹn..
wikipedia
yo
Bí kò bá tún ní ojútùú níbẹ̀, a jẹ́ pé ó di tílùú ní yẹn ọba ló máa ń dájọ́ irú èyí nígbà náà.Tí a bá kà á ní ẹni , èjì ó di ọba mẹ́sàn án tó ti jẹ láti ìgbà tí wọ́n ti dé sí Abẹ́òkúta..
wikipedia
yo
Ṣugbọn, gbogbo wọn tún ṣì wà lábẹ́ Aláké gẹ́gẹ́ bíi ọba gbogbo gbọ́ ni..
wikipedia
yo
Ní ti òye tó kù nílùú, ó ní agbára tí wọ́n fún ìlú kọ̀ọ̀kan láti fi olóyè sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹgba òwú ló sì ń yan ẹkẹrin ìlú.Ọpọlọpọ eniyan jàǹkànjàǹkàn tó ti fi ẹ̀mí wọn wu ewu fún ẹgba ni wọ́n máa ń ranti ninu gbogbo orin wọn..
wikipedia
yo
Irú àwọn báyìí ni sọ́deke, Lisabi, Efunroye, tinúmaakati ati Ogundipé Alátiṣe..
wikipedia
yo
Àwọn Ẹ̀gbá kò kọ́ iyán wọn kéré wọn kò sì yé bu ọlá fún wọn bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti kú.Oríṣìí ètò ìjọba mẹ́rin ọ̀tọ̀òótọ́ ni ó ti kọjá ní ilẹ̀ Ẹ̀gbá kí a tó bọ́ sí èyí tí a wà lóde òní..
wikipedia
yo
Ètò ìbílẹ̀ lábẹ́ àṣẹ Ògbóni àti Parakoyi 1830–1865Ẹ̀gbá United Board of Management 1865-1898 United Government (Ìjọba Ẹ̀gbá) 1898 – 1914Ẹ̀gbá Native Administration (Ìjọba ìbílẹ̀) 1914 – 1960 Àwọn Ẹ̀gbá Iṣẹ́ Iṣẹ́ Ajé ni àwọn Ẹ̀gbá ń mú ṣe nínú ìlú..
wikipedia
yo
Yàtọ̀ sí iṣẹ́ àgbẹ̀ tó jẹ́ tajá tẹran ló ń ṣeé wọ́n fẹ́ràn láti máa dá aró, wọ́n mọ̀ nípa àdìrẹ ẹlẹ́kọ dáadáa..
wikipedia
yo
Àwọn abo ilẹ̀ Saró ni ó jẹ́ kí ọ̀rọ̀ owó ṣíṣe yìí túbọ̀ gbilẹ̀ tó bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Kò sí ìlú kan tí kò ní ọjà tirẹ̀, ṣùgbọ́n àwọn ọjà ń la kan wà tó ti di ti gbogbo gbọ́..
wikipedia
yo
Irú àwọn ọja báyìí ni itokú, Ita Elega, Ọjà Ọba àti ìbẹ̀kòkó..
wikipedia
yo
Paríparí rẹ̀ àwọn ẹgba fẹ́ràn láti máa kọrin lásán.Yálà kíkọ̀ tá gẹ́gẹ́ bí alágbe tàbí ìfẹ́ láti máa kọrin lásán..
wikipedia
yo
Gbogbo ohun tó sì ti ṣẹlẹ̀ sí àwọn baba ńlá wọn ni wọ́n máa ń mú lọ ninu orin wọn pàápàá.Ìbáṣepọ̀ tó wà láàrin àwọn ẹ̀yà Ẹ̀gbá a ti sọ pé kaluku ẹ̀yà Ẹ̀gbá ló ń dá ọmú ìyá rẹ̀ gbé, sibẹ, kò ṣàìsí ìbáṣepọ̀ díẹ̀ láàárín wọn.Lọ́nà kinni, gbogbo Ẹ̀gbá ló gba Abeokuta sí ìlú wọn.Wọ́n ní ilé níbẹ̀, ṣùgbọ́n wọn a máa lọ sí ẹ̀yìn odi ìlú láti lọ múlẹ̀ oko..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ irú oko ẹ̀yìn odi ìlú báyìí ló ti di ìlú fún wọn..
wikipedia
yo
Ètò abúlé wọ́ pọ̀, ó sì gún régé, baálẹ̀ tàbí ọlọ́rọ̀kó (olórí oko) ni ó wà ní ipò owó jùlọ.Bákan náà ló jẹ́ pé gbogbo wọn ló jọ ń bu ọlá fún àwọn ẹni ńlá wọn..
wikipedia
yo
Kò sí pé apá kan kò ka àwọn ẹni àna yìí wọ̀nyìí kún.Ọ̀rọ̀ tún jẹ́ ẹ̀sìn kan tó so wọ́n pọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ọlọ́rọ̀ ìlú kan lè mú ọ̀rọ̀ wọn dé ìlú mìíràn láìsí ìjà láìsí ìta..
wikipedia
yo
Lóòótọ́, ìlú kọ̀ọ̀kan ló ní òrìṣà tirẹ̀ tó ṣe pàtàkì, fún àpẹẹrẹ, àwọn Òwu ló ní Ọ̀tọ̀kàmàmà àti Ẹ̀lukú..
wikipedia
yo
Àwọn odò ọ̀nà lọ ni agẹmọ, àwọn ìbára lọ ni gẹ̀lẹ̀dẹ́..
wikipedia
yo
Ó máa ń ṣẹlẹ̀ ní ọ̀pọ̀ ìgbà pé tí ìlú kan bá parí ọdún tiwọn lónìí, tí àdúgbò mìíràn lè bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ keje ẹ̀..
wikipedia
yo
Èyí kò sì yí padà láti ọjọ́ pípẹ́ wá.Ọjà kan náà ni wọ́n jọ ń ná, oúnjẹ tí wọ́n ń jẹ ní Ake ni wọ́n ń jẹ ní oko..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ń jẹ́ ṣapala kókó, Ewe, àwùjẹ̀ àti Èsúrú.”Mo lérò pé pẹ̀lú gbogbo àlàyé mi òkè yìí ìrànlọ́wọ́ ni yóò jẹ́ fún àwọn ohun tí a ó ó máa kàn nínú orin Ogho níwájú, àwọn ọ̀rọ̀ tí ìbá sì rú ni lójú tẹ́lẹ̀ ni yóò di ohun tí yóò tètè yẹ ni”.Àwọn ìtọ́kasíìlú ìpínlẹ̀ Nàìjíríààwọn ìlú àti abúlé ní Ìpínlẹ̀ Ògùn..
wikipedia
yo
Eko je ounje ti o gbajumo ni Naijiria, ti won si n fi agbado, ọkà tabi jéró se..
wikipedia
yo
Bí wọ́n bá fẹ́ sẹ́ ògì, wọ́n a rẹ àgbàdo,, ọkà tàbí jéró sínú omi fún ọjọ́ méjì sí mẹ́ta kí wọ́n tó lọ̀ ọ́, lẹ́yìn náà, wọn ó fi kalẹ̀ fún bí ọjọ́ mẹ́ta míràn láti kán, lẹ́yìn èyí, wọ́n lè sẹ́ ẹ..
wikipedia
yo
Wọn ma ń fi àkàrà, mọ́in mọ́in àti àwọn oúnjẹ miran mu ògì.Àwọn itọrisiìjìmeje onjẹ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ jẹ́kí á tún bọ̀ sowọ́pọ̀ láti gbé ògo ilẹ̀ Yorùbá ga.Inú mi dùn púpọ̀ sí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀ẹ̀ti kẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n sì jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Yorùbá yálà nílẹ̀ Yorùbá tàbí ní òkè òkun bá lè bẹ̀rẹ̀ láti máa kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú àwọn àròkọ wọn ní èdè abínibí wà nítorí òní kọ́ àmọ́ nítorí ọjọ́ ọ̀la kí àwọn ọmọ tí wọn kò ì tíì bí lè rí nǹkan kà nípa gbogbo ohun mẹ́rẹ̀ mẹ́rẹ̀ tí ó ń ṣẹlẹ̀ jákè jádò àgbáyé.Tí a bá wọ àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní máa gbérí níwọ̀n ọgbọ̀n ọdún sẹ́yìn a rí wí pé púpọ̀ nínú wọn ni wọ́n fi èdè abínibí kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn, kòsí iṣẹ́ìwádìí kan tí wọ́n ṣe tí wọn kò kọ́ ní èdè wọn bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé èdè Gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n gbà fi ṣe ìwádìí náà.Ó seni járí láti máa pàdé àwọn ara ilẹ̀ nílú òyìnbó kí wọ́n máa fara pamọ́ kí á máa bá pè wọ́n ní ọmọ Yorùbá.Ogun lósún àwọn Olùkọ́ni nílú Òyìnbó ni wọ́n jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Yorùbá ṣùgbọ́n pẹ̀lú gbogbo akitiyan wọn kò sí ọ̀kan ṣoṣo nínú iṣẹ́ ìwádìí wọn pẹ̀lú àròkọ tí ó wà ní èdè Yorùbá-kí ló dé?Ọ̀rọ̀ tán lẹ́nu ṣùgbọ́n ó pọ̀ níkùn,títí di ọjọ́ mìíràn ọjọ́ ire,Èmi ni tiyín ní tòótọ́,ọmọba Ontì Olusegunon Oluvadúláwọ̀. Àkíyèsí pàtàkì- tí ẹ bá ní ohun láti sọ nípa àròkọ yìí, ẹ̀yin náà lè bọ́sí gbàgede gbàgede Wikipedia. Jàgídíjàgan..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè tókan àwọn ìpínlẹ̀ Amẹ́ríkà tàbí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (USA tàbí US ní ṣókí ní Gẹ̀ẹ́sì), tàbí Amẹ́ríkà ní ṣókí, jẹ́ orílẹ̀-èdè ìjọba àpapọ̀ Olómìnira pẹ̀lú ìwé-òfin ìbágbépọ̀ tí ó ní ãdọ́ta ìpínlẹ̀, agbègbè ìjọba-àpapọ̀ kan àti agbègbè mẹ́rìnlá, tí ó wà ní Àríwá Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ile rẹ fẹ lati okun pàsífìkí ni apa iwoorun de Okun Atlantiki ni apa ilaọrun..
wikipedia
yo
O ni bodè pẹ̀lú ilẹ̀ Kánádà ní apá àríwá àti pẹ̀lú Mekṣíkọ̀ ní apá gúúsù..
wikipedia
yo
Ipinle Alaska wà ní àríwáìwọ̀òrùn, pẹ̀lú Kánádà ní Ilaorun rẹ̀ àti Rọ́ṣíà ní ìwọ̀òrùn níwájú Bering Strait..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè àwọn ìpínlẹ̀ Koka tún ní ọpọlọpọ agbègbè ní Kari530 àti pàsífìkí.pẹ̀lú 3.79 ẹgbẹgbẹ̀rún ìlọ́poméjì máìlì (9.83 million km) àti iye tó ju 309 ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàn lọ, àwọn ìpínlẹ̀ ààbọ̀odò jẹ́ orílẹ̀-èdè tótóbijùlọ tàbí kẹrin bíi àpapọ̀ iye ààlà ààlà, àti ìkẹta tó bíi ààlà àti bí àwọn olùgbé..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ kan nínú àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé tó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀yà ènìyàn àti asàpúpọ̀, èyí jẹ́ nítorí ìkórèòkèrè láti ọ̀pọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè..
wikipedia
yo
Okòwò àwọn ìpínlẹ̀ odòkùn ni okòwò orílẹ̀-èdè tó tóbijùlọ lágbàyé, pẹ̀lú ìdíye màmá 2009 tó jẹ́ $14.3 ẹgbẹgbẹ̀kẹta (ìdámẹ́rin Mamadou olórúkọ lágbàyé àti ìdámárùn pátápátá fún ìpín agbára ìrajà ìrajààwọn ènìyàn abínibí tí wọ́n wá láti àsíá ti bùdó sí orí ibi tí orílẹ̀-èdè àwọn ìpínlẹ̀ Joṣuakà wà lóní fún ẹgbẹ̀rún lọ́pọ̀ ọdún..
wikipedia
yo
Àwọn olùgbé abínibí ará Amẹ́ríkà dín níye gidigidi nítorí àrùn àti ìgbógunti lẹ́yìn ìbápàdé àwọn ará Europe..
wikipedia
yo
Orilẹ-ede awọn ipinlẹ aṣálẹ̀ka jẹ didasilẹ̀ latọwọ awọn ileàmúsìn mẹtala ti Britani to bùdó si ẹgbẹ Okun Atlantiki..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ 4 oṣù keje, 1776, wọ́n ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìlòlọ́mọ, èyí kéde ẹ̀tọ́ wọn fún ikọ̀ araẹni àti ìdásílẹ̀ ìṣọ̀kan aláfọwọ́sowọ́pọ̀ wọn..
wikipedia
yo