cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
“Fún ẹni tó bá ra oúnjẹ láti ilẹ̀ òkèèrè, yálà nípa owó naira sí dọ́là, tàbí owó naira si Cfà, tàbí ohunkóhun tí ẹ bá fi ṣe pàsírpààrọ̀ owó naira, bí ẹ bá ra oúnjẹ náà, ẹ kò lè tà á ní owó kékeré.” Ọ̀mọ̀wé Kání..
bbc
yo
Ó ní ohun tí ìjọba yóo ṣe ni pé, wọ́n máa dínwó àwọn oúnjẹ náà, bí àpẹẹrẹ tí oúnjẹ kan bá jẹ́ ẹgbẹrun mẹ́wàá, ìjọba yóo tà á ní ẹgbẹrun meje tabi ẹgbẹrun mẹjọ.
bbc
yo
“Fún ẹni tó bá ra oúnjẹ láti ilẹ̀ òkèèrè, yálà nípa owó naira sí dọ́là, tàbí owó naira si Cfà, tàbí ohunkóhun tí ẹ bá fi ṣe gbórpààrọ̀ owó naira, bí ẹ bá ra oúnjẹ náà, ẹ kò le tà á ní owó kékeré.” Ọ̀mọ̀wé kani.
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé Muhammad Suleman kani jẹ kó di mímọ̀ pé bi íse àpapọ̀ bá fẹ́ẹ́ mú ìdẹ̀rùn bá aráàlú, àfi kí wọ́n fòfin de àwọn oúnjẹ ilẹ̀ òkèèrè tí wọ́n lè rí ní Nàìjíríà..
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé Muhammad Suleman kani jẹ kó di mímọ̀ pé bi íse àpapọ̀ bá fẹ́ẹ́ mú ìdẹ̀rùn bá aráàlú, àfi kí wọ́n fòfin de àwọn oúnjẹ ilẹ̀ òkèèrè tí wọ́n lè rí ní Nàìjíríà.
bbc
yo
Gẹ́gẹ́ bó ṣe sọ, ó ní bi ìjọba bá gbé irú ìgbésẹ̀ báyìí, ó yẹ ki wọn tún ṣiṣẹ́ lórí iná mọ̀nàmọ́ná, ki ohun gbogbo lè lọ bó ti tó..
bbc
yo
Ó ní ìgbésẹ̀ yóò ran àwọn èèyàn tí wọ́n ríi pé owó oṣù òṣìṣẹ́ kò yí padà pẹ̀lú bí ètò ọrọ̀ ajé ṣe rí lọ́wọ́, àti pé àwọn oníṣòwò náà ń kojú àìta ọjà wọn nítorí pé agbára káká làwọn èèyan fi ń rí owó láti wọ inú ọjà.
bbc
yo
Gẹ́gẹ́ bó ṣe sọ, ó ní bi Ìjọba bá gbé irú ìgbésẹ̀ báyìí, ó yẹ ki wọn tún ṣiṣẹ́ lórí iná mọ̀nàmọ́ná, ki ohun gbogbo lè lọ bó ti tọ́.
bbc
yo
Bákan náà ló tún rọ Ààrẹ láti gbé ìgbésẹ̀ nípa ṣíṣe ohun tó yẹ, èyí tí yóò mú Nàìjíríà kúrò nínú wàhálà tọ̀ wá báyìí..
bbc
yo
Bákan náà ló tún rọ Ààrẹ láti gbé ìgbésẹ̀ nípa ṣíṣe ohun tó yẹ, èyí tí yóò mú Nàìjíríà kúrò nínú wàhálà tọ̀ wa báyìí.
bbc
yo
Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó sọ pé kí ìjọba mú àwọn ìlérí rẹ̀ tó ṣe nígbà tí wọ́n yọ owó ìrànwọ́ orí epo ṣẹ, nípa fífi ọwọ́ kún owó oṣù, ìgbáyégbádùn àwọn agbègbè àti àtúnkọ́ ilẹ̀ ìfọpo AdkWalwal..
bbc
yo
Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó sọ pé kí ìjọba mú àwọn ìlérí rẹ̀ tó ṣe nígbà tí wọ́n yọ owó ìrànwọ́ orí epo ṣẹ, nípa fífi ọwọ́ kún owó oṣù, ìgbáyégbádùn àwọn agbègbè àti àtúnkọ́ ilẹ̀ ìfọpo AdkWalra.
bbc
yo
Gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ nípa ìpèsè oúnjẹ náà tún ṣe sọ, ó ní ìgbésẹ̀ láti kó oúnjẹ wọlé láti orílẹ̀èdè míràn jẹ́ èyí tó dára, ṣùgbọ́n ṣá, ó ṣe pàtàkì fún ìjọba láti tọpinpin bí ètò òhun yóò ṣe lọ láti ṣe aráàlú ní àǹfààní..
bbc
yo
Gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ nípa ìpèsè oúnjẹ náà tún ṣe sọ, ó ní ìgbésẹ̀ láti kó oúnjẹ wọlé láti orílẹ̀èdè míràn jẹ èyí tó dára, ṣùgbọ́n ṣá, ó ṣe pàtàkì fún ìjọba láti tọpinpin bí ètò òhun yóò ṣe lọ láti ṣe aráàlú ní àǹfààní.
bbc
yo
Ó ní “Àwọn iléeṣẹ́ elétò ààbò ní láti fojú sílẹ̀ nítorí ìwà àwọn ọmọ Nàìjíríà, ẹ lè gbé oúnjẹ náà wọlé tán, kí ẹ wá ríi pé àwọn èèyàn ti bẹ̀rẹ̀ síí ṣe pàṣípààrọ̀ báàgì oúnjẹ náà, wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ síí gbé lọ sáàrin ọjà láti tà á.".
bbc
yo
Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó sọ pé kí ìjọba mú àwọn ìlérí rẹ̀ tó ṣe nígbà tí wọ́n yọ owó ìrànwọ́ orí epo ṣẹ, nípa fífi ọwọ́ kún owó oṣù, ìgbáyégbádùn àwọn agbègbè àti àtúnkọ́ ilẹ̀ ìfọpo kẹtàkWal.
bbc
yo
Ó ní “Àwọn iléeṣẹ́ elétò ààbò ní láti fojú sílẹ̀ nítorí ìwà àwọn ọmọ Nàìjíríà, ẹ lè gbé oúnjẹ náà wọlé tán, kí ẹ wá ríi pé àwọn èèyàn ti bẹ̀rẹ̀ síí ṣe pàṣípààrọ̀ báàgì oúnjẹ náà, wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ síí gbé lọ sáàrin ọjà láti tà á.” Bákan náà ló tún sọ pé ìjọba kò gbọdọ̀ ṣe àṣìṣe láti pín àwọn oúnjẹ náà nípasẹ̀ àwọn gómìnà, nítorí pé kò sí àṣeyọrí nínú èyí tó ṣẹlẹ̀ sẹ́yìn..
bbc
yo
Ó ní “Àwọn iléeṣẹ́ elétò ààbò ní láti fojú sílẹ̀ nítorí ìwà àwọn ọmọ Nàìjíríà, ẹ lè gbé oúnjẹ náà wọlé tán, kí ẹ wá ríi pé àwọn èèyàn ti bẹ̀rẹ̀ síí ṣe pàṣípààrọ̀ báàgì oúnjẹ náà, wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ síí gbé lọ sáàrin ọjà láti tà á.” Bákan náà ló tún sọ pé ìjọba kò gbọdọ̀ ṣe àṣìṣe láti pín àwọn oúnjẹ náà nípasẹ̀ àwọn gómìnà, nítorí pé kò sí àṣeyọrí nínú èyí tó ṣẹlẹ̀ sẹ́yìn.
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé kani sọ pé láti lè ṣe àṣeyọrí, ìjọba àpapọ̀ ni láti yọwọ́ àwọn gómìnà tàbí àwọn aṣòfin àti àwọn aṣojú-ṣòfin kúrò níbẹ̀..
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé kani sọ pé láti lè ṣe àṣeyọrí, ìjọba àpapọ̀ ni láti yọwọ́ àwọn gómìnà tàbí àwọn aṣòfin àti àwọn aṣojú-ṣòfin kúrò níbẹ̀.
bbc
yo
Ó ní kí ìjọba àpapọ̀ ṣàbójútó ètò ohun fúnra rẹ̀, kí wọ́n sì yan àwọn olóòtọ́ aráàlú láti ṣàbójútó e dáadáa tí wọ́n lè ṣe é pẹ̀lú òtítọ́..
bbc
yo
Ó ní kí ìjọba àpapọ̀ ṣàbójútó ètò ohun fúnra rẹ̀, kí wọ́n sì yan àwọn olóòtọ́ aráàlú láti ṣàbójútó e dáadáa tí wọ́n lè ṣe é pẹ̀lú òtítọ́.
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé Muhammad Kání ṣàlàyé pé ètò ìjọba àpapọ̀ yìí yóò ní ipá fún àwọn ọlọ́jà àti àwọn olókoòwò, bẹ́ẹ̀ ló tún sọ pé ní àwọn orílẹ̀èdè bíi United State, ìjọba máa ń ra oúnjẹ, wọ́n yóò sì já owó rẹ̀ wá sílẹ̀ ní gbogbo ìgbà tí kò bá sí àwọn nǹkan irè oko mọ́..
bbc
yo
Bákan náà ló tún sọ pé ìjọba kò gbọdọ̀ ṣe àṣìṣe láti pín àwọn oúnjẹ náà nípasẹ̀ àwọn gómìnà, nítorí pé kò sí àṣeyọrí nínú èyí tó ṣẹlẹ̀ sẹ́yìn.
bbc
yo
Ọ̀mọ̀wé Muhammad kani ṣàlàyé pé ètò ìjọba àpapọ̀ yìí yóò ní ipá fún àwọn ọlọ́jà àti àwọn olókoòwò, bẹ́ẹ̀ ló tún sọ pé ní àwọn orílẹ̀èdè bíi United State, ìjọba máa ń ra oúnjẹ, wọn yóò sì já owó rẹ̀ wá sílẹ̀ ní gbogbo ìgbà tí kò bá sí àwọn nǹkan irè oko mọ́.
bbc
yo
Ó ní ẹ̀tọ́ yìí kò pin sí ibí yìí nìkan, ó sọ pé irú ìgbésẹ̀ yìí náà ni orílẹ̀èdè Saudi Arabia ń gbé..
bbc
yo
Ó ní ẹ̀tọ́ yìí kò pin sí ibí yìí nìkan, ó sọ pé irú ìgbésẹ̀ yìí náà ni orílẹ̀èdè Saudi Arabia ń gbé.
bbc
yo
“Ní Saudi Arabia, àwọn ìgbà kan wà tó jẹ́ pé àwọn irè oko yìí pọ̀ jù, níṣe ni wọ́n ránṣẹ́ pe àwọn àgbẹ̀ láti má ṣe dá oko mọ̀.
bbc
yo
Wọ́n bèèrè pé èèlò ni àwọn ère wọn, wọ́n sì san án fún gbogbo wọn..
bbc
yo
Wọ́n bèèrè pé èèlò ni àwọn ère wọn, wọ́n sì san án fún gbogbo wọn.
bbc
yo
“Nítorí pé tó bá pọ̀ lápọ̀jù, àdánù ni yóò jẹ́ fún wọn.
bbc
yo
Wọ́n kàn máa dá ọkọ̀ lásán ni, láì rí èrè kankan níbẹ̀.".
bbc
yo
Wọ́n kàn máa dá oko lásán ni, láì rí èrè kankan níbẹ̀.” Ó ní bí ìjọba gbé irú ìgbésẹ̀ yìí, ìfigagbága yóò wà láti lè jẹ́ kí àwọn àgbẹ̀ alábọ́dé já owó irè oko wọn wá sílẹ̀..
bbc
yo
Wọ́n kàn máa dá oko lásán ni, láì rí èrè kankan níbẹ̀.” Ó ní bí ìjọba gbé irú ìgbésẹ̀ yìí, ìfigagbága yóò wà láti lè jẹ́ kí àwọn àgbẹ̀ alábọ́dé já owó irè oko wọn wá sílẹ̀.
bbc
yo
Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ náà sọ pé àìsí ilé ìkó ọjà sí (ware) lè ṣe àkóbá nlá fún oúnjẹ kíkó wọlé, nítorí pé kò sí ibi tí wọ́n lè tọ́jú wọn sí, tó sì máa fa kí ọ̀pọ̀ oúnjẹ bàjẹ́..
bbc
yo
Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ náà sọ pé àìsí ilé ìkó ọjà sí (ware) lè ṣe àkóbá nlá fún oúnjẹ kíkó wọlé, nítorí pé kò sí ibi tí wọ́n lè tọ́jú wọn sí, tó sì máa fa kí ọ̀pọ̀ oúnjẹ bàjẹ́.
bbc
yo
Ní báyìí, ó sọ pé ìjọba kò ní oúnjẹ nílé, wọ́n máa kó oúnjẹ wọlé, ati pé ìbéèrè náà ni pé owó wo ni wọn yóo fi ra àwọn oúnjẹ wọnyi..
bbc
yo
Ní báyìí, ó sọ pé ìjọba kò ní oúnjẹ nílé, wọ́n máa kó oúnjẹ wọlé, ati pé ìbéèrè náà ni pé owó wo ni wọn yóo fi ra àwọn oúnjẹ wọnyi.
bbc
yo
Ó sọ pé ó di dandan fún ìjọba láti yá owó láti fi ra àwọn oúnjẹ..
bbc
yo
Ó ní bí ìjọba gbé irú ìgbésẹ̀ yìí, ìfigagbága yóò wà láti lè jẹ́ kí àwọn agbe alábọ́dé já owó irè oko wọn wá sílẹ̀.
bbc
yo
Ó sọ pé ó di dandan fún ìjọba láti yá owó láti fi ra àwọn oúnjẹ.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Ògbómọ̀sọ́parenttontonline ọ̀gọ̣́rọ̀ àwọn agbe láti ìjọba ìbílẹ̀ Oríire ní agbègbè Ògbómọ̀sọ́ ti pariwo síta lóri ìkọlù àwọn darandaran tó ń wáyé ní lemọ́lemọ́ ní ayika wọn.
bbc
yo
Àwọn àgbẹ̀ náà fi àìdun inú wọn hàn l'Ọjọ́bọ̀, lásìkò tí wọ́n ṣe ìfẹ̀hónúhàn lọ sí ààfin sóun ilẹ̀ Ògbómọ̀sọ́, ọba Abọ́bi Ghandi ọ̀laoye.
bbc
yo
Wọ́n pàrọwà sí ọba aládé náà àti àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ láti gbà wọ́n lọ́wọ́ ìkọlù àwọn ẹni afẹ̀sùnkan náà.
bbc
yo
Aṣojú ẹgbẹ́ àwọn àgbẹ̀ tó lé iwájú ìfẹ̀hónúhàn náà, Aremu ogundare ṣe àlàyé wí pé láti ìlú mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni àwọn àgbẹ̀ náà ti Korajọpọ̀ láti pariwo síta.
bbc
yo
Àwọn ìlú náà ni, Kedo Arigbéyọ, Kedo Salami, àti Mosunfadaka..
bbc
yo
Ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn àgbẹ̀ láti ìjọba ìbílẹ̀ Oríire ní agbègbè Ògbómọ̀sọ́ ti pariwo síta lórí ìkọlù àwọn darandaran tó n wáyé ní lemọ́lemọ́ ní ayika wọn.
bbc
yo
Àwọn ìlú náà ni, kédò arigbéyọ, kẹdò Salami, àti mosùn.
bbc
yo
ogúnléda gbàràta wí pé iranlọwọ ọba aládé naa ni awọn nilo lati dẹkun awọn ikọlu to n ṣe àkóbá fun okoowo ati dukiya wọn..
bbc
yo
OgúnDare gbàràta wi pe iranlọwọ ọba alade naa ni awọn nilo lati dẹkun awọn ikọlu to n ṣe àkóbá fun okoowo ati dukiya wọn.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Ògbómọ̀sọ́ìpẹ̀kunghton ó ní, “Àwọn màálù ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àkóbá fún wa.
bbc
yo
Wàhálà yìí bẹ̀rẹ̀ ní bíi ọdún mẹ́rin sí márùn ún sẹ́yìn.
bbc
yo
A kò gbádùn oko dídà bíi tẹ́lẹ̀ mọ́, gbogbo oko ege tí a gbìn ati káṣú sì ni wọ́n ti dá màálù wò.
bbc
yo
ati bọ àwọn aya ati ọmọ wa ti le koko dé ibi pé a kò rí owó ilé ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ wa san"
bbc
yo
Àti bọ́ àwọn aya àti ọmọ wa ti le koko dé ibi pé a kò ri owó ilé ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ wa san”.
bbc
yo
Aṣojú ẹgbẹ́ àwọn agbe náà fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀ wí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni àwọn ti lọ fi ẹjọ́ sun alága ìjọba ìbílẹ̀ àti iléeṣẹ́ ọlọ́pàá, ṣùgbọ́n pàbó ni ìgbìyànjú wọ́n já sí.
bbc
yo
Ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni àwọn darandaran yìí máa ń ṣa àwọn àgbẹ̀ ní àdá, tí wọn á sì pa ẹnikẹ́ni tó bá gbìyànjú láti dá wọn dúró; ìdí sì nìyìí tí àwọn fi wọ́de wá sí ààfin sóun ilẹ̀ Ògbómọ̀sọ́ láti béèrè fún ìrànwọ́..
bbc
yo
Ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni àwọn darandaran yìí máa ń ṣa àwọn àgbẹ̀ ní àdá, tí wọn á sì pa ẹnikẹ́ni tó bá gbìyànjú láti dá wọn dúró; ìdí sì nìyìí tí àwọn fi wọ́de wá sí ààfin sóun ilẹ̀ Ògbómọ̀sọ́ láti béèrè fún ìrànwọ́.
bbc
yo
Láìpẹ́ yìí ni BBC Yorùbá jábọ̀ ìròyìn lórí pásítọ̀ kan tí àwọn afurasi darandaran pa sínú oko rẹ̀ ní agbègbè Ògbómọ̀sọ́..
bbc
yo
Láìpẹ́ yìí ni BBC Yorùbá jábọ̀ ìròyìn lórí pásítọ̀ kan tí àwọn afurasi darandaran pa sínú oko rẹ̀ ní agbègbè Ògbómọ̀sọ́.
bbc
yo
Orísun àwòrán, Ògbómọ̀sọ́mọ̀ọ́stnline olóògbé náà, Segun Adegboyega táwọn afurasi Fúlàní darandaran ṣekú pa lóko rẹ̀ ní agbègbè gẹ́gẹ́ tó wà ní opopona Ògbómọ̀sọ́ sí ìlú Ìsẹ́yìn ti sọ pé lásìkò tí ó ń kìè FÁWỌN fíràwọ̀ tó da ẹran jẹ́ ọkọ rẹ̀ ni wọ́n gun un ẹbe pa..
bbc
yo
Orísun àwòrán, Ògbómọ̀sọ́mọ̀ọ́stnline olóògbé náà, Segun Adegboyega táwọn afurasi Fúlàní darandaran ṣekú pa lóko rẹ̀ ní agbègbè gẹ́gẹ́ tó wà ní opopona Ògbómọ̀sọ́ sí ìlú Ìsẹ́yìn ti sọ pé lásìkò tí ó ń kìè FÁWỌN fíràwọ̀ tó da ẹran jẹ́ ọkọ rẹ̀ ni wọ́n gun un lọ́bẹ̀ pa.
bbc
yo
Àwọn darandaran náà ni wọ́n kó ẹran wọn jẹ̀ oko pásítọ̀ Adégboyè lọ́jọ́ Ajé ọjọ́ Kọkàndínlógbọn oṣù kínní ọdún yìí tí olóògbé náà sì kojú wọn láti dẹ́kun ìwà ibi wọn..
bbc
yo
Àwọn darandaran náà ni wọ́n kó ẹran wọn jẹ̀ oko pásítọ̀ Adégboyè lọ́jọ́ Ajé ọjọ́ kọ́gbọngbọn oṣù kínní ọdún yìí tí olóògbé náà sì kojú wọn láti dẹ́kun ìwà ibi wọn.
bbc
yo
Ẹ̀gbọ́n Oloogbe náà, Taiwo Adegboyega sọ fún BBC Yorùbá pé “Ilé Èkó ni Pásítọ̀ ṣẹ́gun wa nigba ti iyàwó rẹ pé ẹ lati wá bá àwọn darandaran tó da ẹran wọn gba inú ọkọ iṣu rẹ̀.
bbc
yo
Lẹ́yìn ọ̀rẹyìn ni èmi ẹni tó ni ọkọ bá bọ́ sí ọwọ́ àwọn tó dáràn jẹ̀kọ..
bbc
yo
Lẹ́yìn ọ̀rẹyìn ni ẹ̀mí ẹni tó ní oko bá bọ́ sí ọwọ́ àwọn tó dáràn jẹ̀kọ.
bbc
yo
Olóògbé náà, ṣẹ́gun Adegboyega táwọn afurasi Fúlàní darandaran ṣekú pa lóko rẹ̀ ní agbègbè gẹ́gẹ́ tó wà ní òpópónà Ògbómọ̀sọ́ sí ìlú Ìsẹ́yìn ti sọ pé lásìkò tí ó ń kìlọ̀ fáwọn darandaran tó da ẹran jẹ́ ọkọ rẹ̀ ni wọ́n gún un lọ́bẹ pa.
bbc
yo
Orísun àwòrán, oúnjẹ/Olùtti Images l'Ọjọ́bọ̀ ọ̀sẹ̀ yìí ni Àgbáríjọ ẹgbẹ́ Àwọn Kristẹ́ẹ̀nì àti Mùsùlùmí lórílẹ̀ Nàìjíríà rawọ́ ẹ̀bẹ̀ síjọba àpapọ̀ láti wá ọ̀nà àbáyọ sí ìṣòro ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ tó ń kojú aráàlú.
bbc
yo
Bí ìgbé ayé ṣe ń fi ojoojúmọ́ lọ sókè lásìkò yìí, bẹ́ẹ̀ ni ọ̀wọ́ngógó ń bá oúnjẹ, tó sì ń kọ ọmọ Nàìjíríà lóminú púpọ̀.
bbc
yo
Ẹgbẹ́ Àwọn Mùsùlùmí àti Uula lẹkùn nipinle Kaduna ati egbe awon BisAláyọ̀ lẹkùn Àárín gbùngbùn Ariwa ati Gúúsù-Iwọ̀-Oòrùn Orílẹ̀èdè Nàìjíríà sọ pé ebí Ọ̀ru fọwọ́ Kẹ́kẹ́ ló ń pa aráàlú lásìkò yìí.
bbc
yo
Ẹgbẹ́ Àwọn Ìmáàmù Ni Kadanu Pàrọwà si Gomina UBA Sani láti pàṣẹ fún àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tàlélógún nipinle naa láti pèsè ounjẹ ìrànwọ́ fún àwọn aráàlú láwọn agbègbè wọn..
bbc
yo
L'Ọjọ́bọ̀ ọ̀sẹ̀ yìí ni Àgbáríjọ ẹgbẹ́ àwọn Kristẹ́ẹ̀nì àti Mùsùlùmí lórílẹ̀ Nàìjíríà rawọ́ ẹ̀bẹ̀ síjọba àpapọ̀ láti wá ọ̀nà àbáyọ sí ìṣòro ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ tó ń kojú aráàlú.
bbc
yo
Ẹgbẹ́ Àwọn Mùsùlùmí àti Uula lẹkùn nipinle Kaduna ati egbe awon BisAláyọ̀ lẹkùn Àárín gbùngbùn Ariwa ati Gúúsù-Iwọ̀-Oòrùn Orílẹ̀èdè Nàìjíríà sọ pé ebí Ọ̀rujà fowó Kẹ́kẹ́ ló ń pa aráàlú lásìkò yìí.
bbc
yo
Ẹgbẹ́ Àwọn Ìmáàmù ni kadanu pàrọwà sí Gómìnà UBA Sani láti pase fún àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ paro nipinle naa láti pese ounjẹ ìrànwọ́ fún àwọn aráàlú làá agbègbè wọn.
bbc
yo
Bakan naa, awon bíṣọ́ọ̀bù Kátólíìkì ni Ẹkùn Ibadan, ìyẹn Ibadan Ecclesiastical Province sọ pe igbé ayé kò fẹ́ẹ́ rọrùn fún aráàlú pèlú ọ̀wọ́ngógó àti ebi tó wà níta..
bbc
yo
Bákan náà, àwọn bíṣọ́ọ̀bù Kátólííkì ní ẹkùn Ìbàdàn, ìyẹn Ìbàdàn Ecclesiastical Province sọ pé ìgbé ayé kò fẹ́ẹ́ rọrùn fún aráàlú pẹ̀lú ọ̀wọ́ngógó àti ẹbí tó wà níta.
bbc
yo
Wọ́n ní kí ìjọba tètè gbé ìgbésẹ̀ tì yóò fòpin sí ìṣòro àìrí oúnjẹ jẹ lásìkò..
bbc
yo
Wọ́n ní kí ìjọba tètè gbé ìgbésẹ̀ tì yóò fòpin sí ìṣòro àìrí oúnjẹ jẹ lásìkò.
bbc
yo
deó*. The preCarious Socitai-Economic situation prevalent in the country, saying that "the ship of state is fóundering
bbc
yo
Ẹgbẹ́ Àwọn Ìmáàmù ni kadanu pàrọwà sí Gómìnà UBA Sani láti pase fún àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ paro nipinle naa láti sèsè ounjẹ ìrànwọ́ fún àwọn aráàlú làwọn agbègbè wọn.
bbc
yo
Deó*. The PreCarious Socid-Economic situation Prevalent in the country, saying that "the ship of state is fóundering." Ẹkún náà tí àwọn ìlú bíi Ìbàdàn Archdiocese, Ìlọrin, Ondo, Oyo, Èkìtì, àti Òṣogbo Dioceses wà lábẹ́ rẹ̀ ni wọ́n sọ èyí lásìkò ìpàgọ́ tí wọ́n ṣe nílùú Ìbàdàn láìpẹ́ yìí ní jùbí ju Conference Centre, Ìbàdàn..
bbc
yo
Deó*. The PreCarious Socid-Economic situation Prevalent in the country, saying that "the ship of state is fóundering." Ẹkún náà tí àwọn ìlú bíi Ìbàdàn Archdiocese, Ìlọrin, Òndó, Ọ̀yọ́, Èkìtì, àti Òṣogbo Dioceses wà lábẹ́ rẹ̀ ni wọ́n sọ èyí lásìkò ìpàgọ́ tí wọ́n ṣe nílùú Ìbàdàn láìpẹ́ yìí ní jùbí ju Conference Centre, Ìbàdàn.
bbc
yo
Orísun àwòrán, BBC/JEnelat Olawale àwọn ìmáàmù nínú ọ̀rọ̀ wọn Lásìkò ìpàdé àwọn oníròyìn tí wọ́n pè ní Olú-ìyá ijó jà'atu Nasril Islam (Ìrántíníye) tó wà nílùú Kaduna jẹ́ kó di mímọ̀ pé yóò léwu púpọ̀ bí ìjọba bá gbàgbé àwọn mẹ̀kúnnù tí ebi ń pa lásìkò yìí..
bbc
yo
Orísun àwòrán, BBC/JEnelat Olawale àwọn ìmáàmù nínú ọ̀rọ̀ wọn Lásìkò ìpàdé àwọn oníròyìn tí wọ́n pè ní Olú-ìyá ijó jà'atu Nasril Islam (Ìrántíníye) tó wà nílùú Kaduna jẹ́ kó di mímọ̀ pé yóò léwu púpọ̀ bí ìjọba bá gbàgbé àwọn mẹ̀kúnnù tí ebi ń pa lásìkò yìí.
bbc
yo
Àwọn alakoso ijo naa, Sheikh Aminu umDAH ati Sheikh Idris Muhammad sa-gari sọ pe ẹkun ti aráàlú n sun ti je ohun to yẹ ki ijoba tete wa ona abyo yo ko too pẹ ju..
bbc
yo
Ẹkun naa ti awon ilu bii Ibadan Archdiocese, Ilorin, Ondo, Oyo, Ekiti, ati Oso Dioceses wa labẹ rẹ ni won so eyi lasiko ìpàgọ́ ti won se nílùú Ibadan laipẹ yii ni jubi Conference Centre, Ibadan.
bbc
yo
Awọn alakoso ijo naa, Sheikh Aminu umDAH ati Sheikh Idris Muhammad sa-gari sọ pe ẹkun ti aráàlú n sun ti jẹ ohun to yẹ ki ijoba tete wa ona abyo yo ko too pẹ ju.
bbc
yo
Ninu oro won, "awa egbe awon Imáàmù ati Uula nipinle Kaduna ti dide lati soro lori Ìṣòro ati Ebi to n doju kọ aráàlú nitori awon agbekale ijoba lori yíyọ Owo Ìrànwọ́ Ori epo..
bbc
yo
Ninu oro won, "awa egbe awon ìmáàmù ati Uula nipinle Kaduna ti Dide lati soro lori ìṣòro ati ebi to n doju ko ijoba nitori awon agbekale ijoba lori yíyọ owo ìrànwọ́ ori epo.
bbc
yo
“A ń rọ ìjọba ìpínlẹ̀ yìí láti gbé ètò dìde, kí wọ́n sì sọ fáwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ láti pèsè ìrànwọ́ fún aráàlú káàkiri ìgbèríko àti agbègbè wọn.".
bbc
yo
Awon Imáàmù ninu oro won lasiko ipade awon oniroyin ti won pe ni Olu-Iya ijo Jam'atu Nasril Islam (Ìrántíníye) to wa nílùú Kaduna je ko di mimo pe yoo lewu pupo bi ijoba ba gbagbe awon mẹ̀kúnnù ti ebi n pa lasiko yii.
bbc
yo
“A ń ro ìjọba ìpínlẹ̀ yìí láti gbé ètò dìde, kí wọ́n sì sọ fáwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ láti pèsè ìrànwọ́ fún aráàlú káàkiri ìgbèríko ati agbègbè wọn.” Wọ́n ní àjọṣepọ̀ ati ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ní gbogbo ẹ̀ka ìjọba ló ṣe pàtàkì lásìkò yìí láti ríi pé ọ̀nà àbáyọ àtìgbàdégbà wà fún ìpèníjà tí aráàlú ń kojú..
bbc
yo
“A ń ro ìjọba ìpínlẹ̀ yìí láti gbé ètò dìde, kí wọ́n sì sọ fáwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ láti pèsè ìrànwọ́ fún aráàlú káàkiri ìgbèríko ati agbègbè wọn.” Wọ́n ní àjọṣepọ̀ ati ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ní gbogbo ẹ̀ka ìjọba ló ṣe pàtàkì lásìkò yìí láti ríi pé ọ̀nà àbáyọ àtìgbàdégbà wà fún ìpèníjà tí aráàlú ń kojú.
bbc
yo
“pínpín èròjà oúnjẹ àti owó ìrànwọ́ tí ìjọba àpapọ̀ ṣagbátẹrù rẹ̀ fún àwọn aṣojú aráàlú nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin àti ìjọba ìpínlẹ̀ ti jẹ́ kí àwọn èèyàn máa lá àdojúkọ ńlá kọjá.
bbc
yo
“pínpín èròjà oúnjẹ àti owó ìrànwọ́ tí ìjọba àpapọ̀ ṣagbátẹrù rẹ̀ fún àwọn aṣojú aráàlú nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin àti ìjọba ìpínlẹ̀ ti jẹ́ kí àwọn èèyàn máa lá àdojúkọ ńlá kọjá “Ẹkún tí àwọn èèyàn wá ń sun yẹ kí ọ̀nà àbáyọ tètè wà.
bbc
yo
A wá ń rọ gómìnà Sani àti ìjọba Àpapọ̀ láti Ìpínlẹ̀ Kaduna, kí wọ́n tètè gbé ìgbésẹ̀ pàjáwìrì nípa pínpín oúnjẹ ìrànwọ́ fún aráàlú káàkiri ìpínlẹ̀ náà.".
bbc
yo
A wá ń rọ gómìnà Sani àti ìjọba àpapọ̀ láti Ìpínlẹ̀ Kaduna, kí wọ́n tètè gbé ìgbésẹ̀ pàjáwìrì nípa pínpín oúnjẹ ìrànwọ́ fún aráàlú káàkiri ìpínlẹ̀ náà.” Orísun àwòrán, Getty Images.
bbc
yo
Wọ́n ní àjọsepọ̀ àti ìfọwọ́ṣowọ́pọ̀ ní gbogbo ẹ̀ka ìjọba ló ṣe pàtàkì lásìkò yìí láti ríi pé ọ̀nà àbáyọ àtìgbàdégbà wà fún ìpèníjà tí aráàlú ń kojú.
bbc
yo
A wá ń rọ gómìnà Sani àti ìjọba Àpapọ̀ láti Ìpínlẹ̀ Kaduna, kí wọ́n tètè gbé ìgbésẹ̀ pàjáwìrì nípa pínpín oúnjẹ ìrànwọ́ fún aráàlú káàkiri ìpínlẹ̀ náà.” Orísun àwòrán, Getty Images alága ẹgbẹ́ àwọn Bíṣọ́ọ̀bù, Jehovahrendi àgbà lékè Gabriel Aaberin ti wá di bùba àwọn ajínigbé àti apànìyànjayé, tó sì ní àwọn ẹ̀rí rẹ̀ ní ti àwọn ọba alayé tí àwọn àmọ̀òkú pa dànù láìpẹ́ láìpẹ́ yìí..
bbc
yo