cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
A wá ń rọ gómìnà Sani àti ìjọba Àpapọ̀ láti Ìpínlẹ̀ Kaduna, kí wọ́n tètè gbé ìgbésẹ̀ pàjáwìrì nípa pínpín oúnjẹ ìrànwọ́ fún aráàlú káàkiri ìpínlẹ̀ náà.” Orísun àwòrán, Getty Images alága ẹgbẹ́ àwọn Bíṣọ́ọ̀bù, Jehovahrendi àgbà lékè Gabriel Aaberin ti wá di bùba àwọn ajínigbé àti apànìyànjayé, tó sì ní àwọn ẹ̀rí rẹ̀ ní ti àwọn ọba alayé tí àwọn àmọ̀òkú pa dànù láìpẹ́ láìpẹ́ yìí.
bbc
yo
O ni ẹdun okan lo je lori bi won se pa ẹlẹ́sùn tilùú esun Ekiti, oba David Babatunde Ogunsakin, ati the Olujo tilùú ìmòjò Ekiti, Oba Samuel Olusola nipinle Ekiti, pelu bi won se ji awon akekoo ati oluko gbe ba ni lokan je pupo..
bbc
yo
“Ẹkún tí àwọn èèyàn wá ń sùn yẹ kí ọ̀nà àbáyọ tètè wà.
bbc
yo
O ni ẹdun okan lo je lori bi won se pa ẹlẹ́sùn tilùú esun Ekiti, oba David Babatunde Ogunsakin, ati the Olujo tilùú ìmòjò Ekiti, Oba Samuel Olusola nipinle Ekiti, pelu bi won se ji awon akekoo ati oluko gbe ba ni lokan je pupo.
bbc
yo
Bakan naa ni abẹ́gunrin tun ni Aja BURÚKÚ NÁÀ LO TÚN KAN ỌBA Peter Segun, olùkọlù Tdie Kokun nipinle Kwara tí wọ́n pàdánù, tí wọ́n sì tún jí ìyàwó àti àwọn méjì míràn gbé salọ..
bbc
yo
Orísun àwòrán, Getty Images alága ẹgbẹ́ àwọn Bíṣọ́ọ̀bù, Jehovahrendi àgbà lékè Gabriel Aaberin ti wá di bùba àwọn ajínigbé àti apànìyànjayé, tó sì ní àwọn ẹ̀rí rẹ̀ ní ti àwọn ọba alayé tí àwọn àmọ̀òkúṣèkà pa dànù láìpẹ́ yìí.
bbc
yo
Bakan naa ni abẹ́gunrin tun ni Aja BURÚKÚ NÁÀ lo tun kan Oba Peter Segun, olukọro Tlùú Kokun nipinle Kwara ti won padanu, ti won si tun ji iyawo ati awon meji miran gbe salọ.
bbc
yo
“Oko orilẹede yìí ti wa n rin lori àgbá àìsí eto aabo bayii, pẹlu ipenija eto ọrọ aje nitori pe ọ̀wọ́ngógó ṣe ba gbogbo nǹkan nipasẹ owo naira, jìbìtì ori ayelujara, aibikita ijọba ati ìmúgbòòrò iwa àjẹbánu..
bbc
yo
Alaga ẹgbẹ awon bíṣọ́ọ̀bù, nípòrendi agba lékè Gabriel Aaberin ti wa di bùba awon ajínigbé ati apaniyanjayé, to si ni awon eri re ni ti awon oba alaye ti awon amoòkúṣẹ́kà pa dànù laipẹ yii.
bbc
yo
“Oko orílẹ̀èdè yìí ti wá ń rìn lórí àgbà àìsí ètò ààbò báyìí, pẹ̀lú ìpèníjà ètò ọrọ̀ ajé nítorí pé ọ̀wọ́ngógó ṣe bá gbogbo nǹkan nípasẹ̀ owó náírà, jìbìtì orí ayélujára, àtiaibikita ìjọba àti ìmúgbòòrò ìwà àjẹbánu.
bbc
yo
“Lojoojumọ ni ìgbé ayé àìsí ìdẹ̀rùn ti wá di tọ́rọ̀fọ́nkálẹ̀ fún àwọn ọmọ Nàìjíríà tí wọ́n ń gbé nínú ìṣẹ́ àti òṣì, èyí tó ń mú kí ọ̀pọ̀ máa gbẹ̀mí ara wọn..
bbc
yo
“Lojoojumọ ni ìgbé ayé àìsí ìdẹ̀rùn ti wá di tọ́rọ̀fọ́nkálẹ̀ fún àwọn ọmọ Nàìjíríà tí wọ́n ń gbé nínú ìṣẹ́ àti òṣì, èyí tó ń mú kí ọ̀pọ̀ máa gbẹ̀mí ara wọn.
bbc
yo
Síwájú síi ló sọ pé ìpèníjà yìí ti wá sọ àwọn aráàlú di ọ̀dájú nítorí ìwà àìláànú àwọn adarí lẹ́ka ètò òṣèlú..
bbc
yo
Síwájú síi ló sọ pé ìpèníjà yìí ti wá sọ àwọn aráàlú di ọ̀dájú nítorí ìwà àìláànú àwọn adarí lẹ́ka ètò òṣèlú.
bbc
yo
Bákan náà ló sọ pé ìgbésẹ̀ ọ̀nà àbáyọ tí ìjọba yóò gbé lásìkò yìí ti pẹ́ jù fún àwọn aráàlú tí wọ́n ti pàdánù ẹ̀mí wọn sọ́wọ́ àwọn àbọ̀n, ajínigbé àti onírúurú àjálù..
bbc
yo
“Oko orílẹ̀èdè yìí ti wá ń rìn lórí àgbà àìsí ètò ààbò báyìí, pẹ̀lú ìpèníjà ètò ọrọ̀ ajé nítorí pé ọ̀wọ́ngógó ṣe bá gbogbo nǹkan nípasẹ̀ owó náírà, jìbìtì orí ayélujára, àìbìkítà ìjọba àti ìmúgbòòrò ìwà àjẹbánu.
bbc
yo
Bákan náà ló sọ pé ìgbésẹ̀ ọ̀nà àbáyọ tí ìjọba yóò gbé lásìkò yìí ti pẹ́ jù fún àwọn aráàlú tí wọ́n ti pàdánù ẹ̀mí wọn sọ́wọ́ àwọn awù, ajínigbé àti onírúurú àjálù.
bbc
yo
Bẹ́ẹ̀ ló rọ ìjọba láti tètè gbé ìgbésẹ̀ tí yóò fòpin sí àwọn ìṣòro wọ̀nyí, kí ọkọ̀ Nàìjíríà má ba à rì sínú agbami òkun..
bbc
yo
Bẹ́ẹ̀ ló rọ ìjọba láti tètè gbé ìgbésẹ̀ tí yóò fòpin sí àwọn ìṣòro wọ̀nyí, kí ọkọ̀ Nàìjíríà má ba à rì sínú agbami òkun.
bbc
yo
Orísun aworan, BBC/others àwọn mọ̀lẹ́bí Táyé Olugbáyé, dẹ́rẹ́bà ilé ẹ̀kọ́ The Apostolic faith Apostolic Montessori School ẹmure Ekiti ti ni ohun ibanujẹ lo je fun idile pe won ko ni anfani lati foju ri òkú Oloogbe fun ètò ìsìnkú.
bbc
yo
Olutayo ọ̀sẹ̀ni, ẹ̀gbọ́n olóògbé ṣàlàyé pé ìpayà, ibànújẹ́ àti iyàwó kíkorò ni iroyin nípa ikú olùgbáyé jẹ́ fún oun àti gbogbo ìdílé.
bbc
yo
Ó ní kété tí ohùn gbọ́ pé wọ́n ti yu àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ sílẹ̀ ní òun mórílé ààfin ọba ṣùgbọ́n ìbànújẹ́ ló jẹ́ fún ọ pé kò sí àbúrò òun níbẹ̀.
bbc
yo
“Gẹ́gẹ́ bíi wọ́n ṣe sọ, tó sì jẹ́ ohun tó bà wá lẹ́rù, pé pẹlu gbogbo nǹkan Tom ṣẹlẹ̀, tó sì jẹ́ pé ó jẹ́ ọkunrin, tó ti mọ gbogbo àṣírí wọn ni wọ́n ṣe ṣẹ́kùpa, tí wọ́n sì tún dáná sun pẹlu..
bbc
yo
Awon molebi Taye Oluwaye, dẹ́rẹ́bà ile eko the Apostolic faith Apostolic Montessori School ẹmure Ekiti ti ni ohun ibanujẹ lo je fun idile pe won ko ni anfani lati foju ri òkú Oloogbe fun eto isinku.
bbc
yo
“Gẹ́gẹ́ bíi wọ́n ṣe sọ, tó sì jẹ́ ohun tó bà wá lẹ́rù, pé pẹlu gbogbo nǹkan Tom ṣẹlẹ̀, tó sì jẹ́ pé ó jẹ́ ọkunrin, tó ti mọ gbogbo àṣírí wọn ni wọ́n ṣe ṣẹ́kùpa, tí wọ́n sì tún dáná sun pẹlu.
bbc
yo
“Ìbànújẹ́ ni ọ̀rọ̀ jẹ́ fún gbogbo ìdílé wa pé ó ti ẹ ní gbọ́rọ̀ àbúrò mi mọ́.” .
bbc
yo
“Ìbànújẹ́ ni ọ̀rọ̀ jẹ́ fún gbogbo ìdílé wa pé ó ti ẹ ní gbọ́rọ̀ àbúrò mi mọ́.” Ọṣẹni wà gbogbo lọ́wọ́ ọba, àárẹ̀, gomina, alága ìbílẹ̀ ati àwọn èso alábò fún gbogbo igbiyanju wọn láti rí pé wọ́n dọ̀la ẹ̀mí àwọn èèyàn..
bbc
yo
“Ìbànújẹ́ ni ọ̀rọ̀ jẹ́ fún gbogbo ìdílé wa pé ó ti ẹ ní gbọ́rọ̀ àbúrò mi mọ́.” Ọṣẹni wà gbogbo lọ́wọ́ ọba, àárẹ̀, gomina, alága ìbílẹ̀ ati àwọn ẹ̀so alábò fún gbogbo igbiyanju wọn láti rí pé wọ́n dọ̀la ẹ̀mí àwọn èèyàn.
bbc
yo
“Adúpẹ́ lọ́wọ́ gbogbo àwọn ìjọ Kristẹni ṣùgbọ́n ó ṣeni laanu..
bbc
yo
“Adúpẹ́ lọ́wọ́ gbogbo àwọn ìjọ Kristẹni ṣùgbọ́n ó ṣeni laanu.
bbc
yo
“Injì tí baba wọn ṣẹ̀ ló ti di eérú ẹnìkan, tó jẹ́ ìyá wọn.".
bbc
yo
“In2 tí baba wọn ṣe ló ti di eérú ẹnìkan, tó jẹ́ ìyá wọn.” ‘Àwọn ajínigbé gba owó lọ́wọ́ wa kí wọ́n tó tú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sílẹ̀’.
bbc
yo
Osẹ̀ni wa gbogbo lọ́wọ́ Oba, Aare, gomina, Alaga ibile ati awon eso alabo fun gbogbo igbiyanju won lati ri pe won dola emi awon eeyan.
bbc
yo
“Ingbogb ti baba wọn se lo ti di eérú ẹnìkan, to je iya won." 'Awon ajínigbé gba owo lowo wa ki won to tu awon akekoo sile' gbajumo osere, fìtílà Igwe toro àforíjìn fun bi o se gbadura ni ìhòhò.
bbc
yo
"Inke ti baba won se lo ti di eérú ẹnìkan, to je iya won." 'Awon ajínigbé gba owo lowo wa ki won to tu awon akekoo sile' gbajumo osere, Ọláìya Igwe toro àforíjìn fun bi o se gbadura ni ihoho okan lara awon omo oloogbe naa, Rufiat Olugbáyé ràwọ̀ Ẹ̀bẹ̀ si Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ekiti pe ko dakun ba awon wa ibi ti won gbe oku baba awon si ki awon le se oórì fun un..
bbc
yo
“Inke ti baba won se lo ti di eérú ẹnìkan, to je iya won." 'Awon ajínigbé gba owo lowo wa ki won to tu awon akekoo sile' gbajumo osere, Ọláìya Igwe toro àforíjìn fun bi o se gbadura ni ihoho okan lara awon omo oloogbe naa, Rufiat Olugbáyé ràwọ̀ Ẹ̀bẹ̀ si Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ekiti pe ko dakun ba awon wa ibi ti won gbe oku baba awon si ki awon le se oórì fun un.
bbc
yo
“Bí ó tilẹ̀ jẹ eérú ni wọ́n rí níbẹ̀ kí á ṣá a kọ̀ kí á le sin wọ́n...Bó jẹ́ egungun ló kù, kí wọn sá bá wa kọ́ ọ.".
bbc
yo
‘Àwọn ajínigbé gba owó lọ́wọ́ wa kí wọ́n tó tú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ sílẹ̀' gbajúmọ̀ òṣèré, Ọláìní Igwe tọrọ àforíjìn fún bí o ṣe gbàdúrà ní ìhòhò ọ̀kan lára àwọn ọmọ olóògbé náà, Rufia olùgbáyé rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkìtì pé kò dákun bá àwọn wá ibi tí wọ́n gbé òkú bàbá àwọn sí kí àwọn lè ṣe oórí fún un.
bbc
yo
“Bí o tilẹ̀ jẹ eérú ni wọ́n rí níbẹ̀ kí á sá à kọ̀ kí a le sin wọ́n…Bó jẹ́ egungun ló kù, kí wọ́n sá bá wa kó o." Rufiat ní ohun tó ń múmú lọ́kàn àwọn báyìí ni kí baba àwọn ní yèrì tí àwọn yóò le máa tọ́ka sí lọ́jọ́ iwájú pé ibi tí wọ́n sin baba àwọn sí nìyí..
bbc
yo
Gbajumọ oṣere, fìtílà Igwe toro àforíjìn fun bi o se gbadura ni ìhòhò lara lara awọn ọmọ Oloogbe naa, Rufia olugbáyé ràwọ̀ ẹbẹ si ijoba ipinle Ekiti pe ko dakun ba awon wa ibi ti won gbe oku baba awon si ki awon le se oórì fun un.
bbc
yo
“Bí o tilẹ̀ jẹ eérú ni wọ́n rí níbẹ̀ kí á sá à kọ̀ kí á le sin wọ́n…Bó jẹ́ egungun ló kù, kí wọ́n sá bá wa kó o." Rufiat ní ohun tó ń múmú lọ́kàn àwọn báyìí ni kí baba àwọn ní yèrì tí àwọn yóò le máa tọ́ka sí lọ́jọ́ iwájú pé ibi tí wọ́n sin baba àwọn sí nìyí.
bbc
yo
Àkọ́bí olóògbé TÓSÌN olùgbáyé ni ó ṣe ni laanu pé Bàbá òun, fi Bàbá sílẹ̀ láyé .
bbc
yo
Ọ̀kan lára àwọn ọmọ olóògbé náà, Rufiat olùgbáyé ràwọ̀ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkìtì pé kò Dákun bá àwọn wá ibi tí wọ́n gbé òkú bàbá àwọn sí kí àwọn lè ṣe àorì fún un.
bbc
yo
Àkọ́bí olóògbé TÓSÌN olùgbáyé ni ó ṣe ni laanu pé Bàbá òun, fi Bàbá silẹ̀ láyé ó ni kàyéfì ni ìròyìn náà kọ́kọ́ jẹ́ fún òun nigbà ti òun gbọ́ si ìṣẹ̀lẹ̀ pé wọn kò ri Bàbá òun ṣùgbọ́n wọ́n rí bàtà àti aṣọ..
bbc
yo
Àkọ́bí olóògbé TÓSÌN olùgbáyé ni ó ṣe ni laanu pé Bàbá òun, fi Bàbá silẹ̀ láyé ó ni kàyéfì ni ìròyìn náà kọ́kọ́ jẹ́ fún òun nigbà ti òun gbọ́ si ìṣẹ̀lẹ̀ pé wọn kò ri Bàbá òun ṣùgbọ́n wọ́n rí bàtà àti aṣọ.
bbc
yo
Tosin, ẹni tó ni ilú Adó Èkìtì ni òun wà nigbà ó gbọ́ nípa ìròyìn naà, tó sì wá si ẹmurẹ̀ pẹ̀lú iyá rẹ̀, tó jẹ́ ìyàwó olóògbé..
bbc
yo
Rufiat ní ohun tó ń múmú lọ́kàn àwọn báyìí ni kí baba àwọn ní rìrì tí àwọn yóò le máa tọ́ka sí lọ́jọ́ iwájú pé ibi tí wọ́n sin bàbá àwọn sí nìyí.
bbc
yo
Àkọ́bí olóògbé TÓSÌN olùgbáyé ni ó ṣe ni laanu pé Bàbá òun, fi Bàbá silẹ̀ láyé ó ni kàyéfì ni ìròyìn náà kọ́kọ́ jẹ́ fún òun nigbà ti òun gbọ́ sí ìṣẹ̀lẹ̀ pé wọn kò ri Bàbá òun ṣùgbọ́n wọ́n rí bàtà àti aṣọ.
bbc
yo
Tosin, ẹni tó ni ilú Adó Èkìtì ni òun wà nigbà ó gbọ́ nípa ìròyìn naà, tó sì wá si ẹmurẹ̀ pẹ̀lú iyá rẹ̀, tó jẹ́ iyàwó olóògbé.
bbc
yo
“Nígbà tí mo dé ilé baba olóògbé náà àwọn náà ni àwọn ti gbọ́ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà.
bbc
yo
“Nígbà tí mo dé ilé baba olóògbé náà àwọn náà ni àwọn ti gbọ́ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà “Ní dédé méjì ooru ni èèyàn kan í mo má fi orúkọ bò ní àṣírí, tó sọ fún pé wọ́n ti tú àwọn èèyàn sílẹ̀ ṣùgbọ́n wọn kò rí baba mi..
bbc
yo
Ó ní kàyéfì ni ìròyìn náà kọ́kọ́ jẹ́ fún òun nígbà tí òun gbọ́ sí ìṣẹ̀lẹ̀ pé wọn kò rí bàbá òun ṣùgbọ́n wọ́n rí bàtà àti aṣọ.
bbc
yo
“Nígbà tí mo dé ilé baba olóògbé náà àwọn náà ni àwọn ti gbọ́ nípa ìṣẹ̀lẹ̀ náà “Ní dédé méjì ooru ni èèyàn kan í mo má fi orúkọ bò ní àṣírí, tó sọ fún pé wọ́n ti tú àwọn èèyàn sílẹ̀ ṣùgbọ́n wọn kò rí baba mi.
bbc
yo
“Èrò ọ̀kan ni pé bóyá ìbò mìíràn ni baba mọ wà, tí mo sì ń sáré bọ̀ sí ìlú ẹmurẹ̀..
bbc
yo
“Èrò ọ̀kan ni pé bóyá ìbò mìíràn ni baba mọ wà, tí mo sì ń sáré bọ́ sí ìlú ẹmurẹ̀.
bbc
yo
“Ní dédé méjì ooru ni èèyàn kan í mo má fi orúkọ bò ní àṣírí, tó sọ fún pé wọ́n ti tú àwọn èèyàn sílẹ̀ ṣùgbọ́n wọn kò rí baba mi.
bbc
yo
Orísun àwòrán, others pásítọ̀ ìjọ aladani kan, ní ìlú ọ̀húnmọ̀ṣọ́ ní Adegboyega kí àwọn afurasi darandaran kan tó ṣẹ́kùpa á.
bbc
yo
Àwọn afurasi darandaran náà ni a gbọ́ pé wọ́n dá jẹ́ ẹran jẹ́ oko pásítọ̀ Adégboyè lọ́jọ́ ajé ọjọ́ kókàndínlọ́gbọ̀n oṣù kinni ọdún yìí tí olóògbé náà sì kójú wọn láti kó ẹran wọn kúrò nínú oko rẹ̀.
bbc
yo
Ìròyìn fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wí pé níṣe làwọn darandaran Fúlàní náà kọjú ìjà sí pásítọ̀ yìí tí wọ́n sì gún un lọ́bẹ títí tí èmi fi bọ́ lára rẹ̀.
bbc
yo
Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ náà làwọn aráàlú mú àwọn afurasi darandaran mẹta tí wọ́n sọ pé wọ́n lọ́wọ́ ninu ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún..
bbc
yo
Pásítọ̀ ijọ alága kan, ni ilú Ògbómọ̀sọ́ ni Adegboyega ki àwọn afurasi darandaran kan tó ṣekúpá a.
bbc
yo
Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ náà làwọn aráàlú mú àwọn afurasi darandaran mẹta tí wọ́n sọ pé wọ́n lọ́wọ́ ninu ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún.
bbc
yo
Lẹsẹkẹsẹ ni wọ́n sì gbé wọn lọ sí ààfin sóun ìlú Ògbómọ̀sọ́, ọba Ghandi ọ̀laoyè òrumogègé kẹta kí kabiyesi tó ní kí wọ́n gbé wọn lọ sí àhámọ́ ọgbà àwọn ọlọ́pàá tó wà ní agbègbè Owode nílùú Ògbómọ̀sọ́..
bbc
yo
Àwọn afurasi darandaran náà ni a gbọ́ pé wọ́n dá jẹ́ ẹran jẹ́ oko pásítọ̀ Adégboyè lọ́jọ́ ajé ọjọ́ kóṣẹ́gbọn oṣù kinni ọdún yìí tí olóògbé náà sì kọjú wọn láti kó ẹran wọn kúrò nínú oko rẹ̀.
bbc
yo
Lẹsẹkẹsẹ ni wọ́n sì gbé wọn lọ sí ààfin sóun ìlú Ògbómọ̀sọ́, ọba Ghandi ọ̀laoyè òrumogègé kẹta kí kabiyesi tó ní kí wọ́n gbé wọn lọ sí àhámọ́ ọgbà àwọn ọlọ́pàá tó wà ní agbègbè Owode nílùú Ògbómọ̀sọ́.
bbc
yo
Orísun àwòrán, BBC/other Taiwo Jacob to je egbon pásítọ̀ Segun Adegboyega tàwọn afurasi Fúlàní darandaran ṣekú pa lóko rẹ̀ ní agbègbè gẹ́gẹ́ tó wà ní òpópónà Ògbómọ̀sọ́ sí ìlú Ìsẹ́yìn ti sọ pé lásìkò tí ó ń kìlọ̀ fáwọn darandaran tó da ẹran jẹ́ oko rẹ̀ ni wọ́n gún un lọ́bẹ pa..
bbc
yo
Orísun àwòrán, BBC/other Taiwo Jacob to je egbon pásítọ̀ Segun Adegboyega tàwọn afurasi Fúlàní darandaran ṣekú pa lóko rẹ̀ ní agbègbè gẹ́gẹ́ tó wà ní òpópónà Ògbómọ̀sọ́ sí ìlú Ìsẹ́yìn ti sọ pé lásìkò tí ó ń kìlọ̀ fáwọn darandaran tó da ẹran jẹ́ oko rẹ̀ ni wọ́n gún un lọ́bẹ pa.
bbc
yo
Ẹ̀gbọ́n olóògbé náà sọ fún BBC Yorùbá pé “Ilé Èkó ni Pásítọ̀ ṣẹ́gun wa nígbà ti lẹ́yìn àríyànjiyàn tó wáyé láàrín olóògbé náà àti àwọn Fúlàní darandaran, ọ̀kan nínú àwọn Fúlàní ohun gún pásítọ̀ Adegboyega lọ́bẹ látẹ̀yìn kí wọ́n tó sálọ..
bbc
yo
Ẹ̀gbọ́n olóògbé náà sọ fún BBC Yorùbá pé “Ilé Èkó ni Pásítọ̀ ṣẹ́gun wà nígbà ti lẹ́yìn àríyànjiyàn tó wáyé láàrín olóògbé náà àti àwọn Fúlàní darandaran, ọ̀kan nínú àwọn Fúlàní ohun gún pásítọ̀ Adegboyega lọ́bẹ̀ látẹ̀yìn kí wọ́n tó sálọ.
bbc
yo
Ọkada ni a fi gbé olóògbé lọ sílé ìwòsàn kò tó gbẹ̀mí mi.’
bbc
yo
Ọkada ni a fi gbé olóògbé lọ sílé ìwòsàn kò tó gbẹ̀mí mi.’‘ Lára àwọn ọ̀dọ́ agbègbè gẹ́gẹ́ níbi tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé ṣàlàyé wí pé,“Pásítọ̀ Adegboyega ti ṣáájú àkókò yìí ni àríyànjiyàn ránpẹ́ pẹ̀lú àwọn Fúlàní ọ̀hún, nítorí Gáà wọn kò jìnnà sí ilé pásítọ̀ Adegboyega..
bbc
yo
Taiwo Jacob to je egbon pásítọ̀ Segun Adegboyega tàwọn afurasi Fúlàní darandaran ṣekú pa lóko rẹ̀ ní agbègbè gẹ́gẹ́ tó wà ní òpópónà Ògbómọ̀sọ́ sí ìlú Ìsẹ́yìn ti sọ pé lásìkò tí ó n kìlọ̀ fáwọn darandaran tó da ẹran jẹ́ oko rẹ̀ ni wọ́n gún un lọ́bẹ pa.
bbc
yo
Ọkada ni a fi gbé olóògbé lọ sílé ìwòsàn kò tó gbẹ̀mí mi.’‘ Lára àwọn ọ̀dọ́ agbègbè gẹ́gẹ́ níbi tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé ṣàlàyé wí pé,“Pásítọ̀ Adegboyega ti ṣáájú àkókò yìí ni àríyànjiyàn ránpẹ́ pẹ̀lú àwọn Fúlàní ọ̀hún, nítorí Gáà wọn kò jìnnà sí ilé pásítọ̀ Adegboyega.
bbc
yo
“Lọ́jọ́ tí pásítọ̀ Adegboyega kú, ìyàwó mi pé mi kí n máa bọ̀ wá sí ilé nítorí wọ́n ti gún pásítọ̀ lọ́bẹ..
bbc
yo
“Lọ́jọ́ tí pásítọ̀ Adegboyega kú, ìyàwó mi pé mi kí n máa bọ̀ wá sí ilé nítorí wọ́n ti gún pásítọ̀ lọ́bẹ.
bbc
yo
Lójú ọ̀nà ni mo ti pàdé àwọn tó ń gbé wọn lọ sí ilé ìwòsàn, kódà ọ̀kadà la lò láti gbé wọn..
bbc
yo
Lójú ọ̀nà ni mo ti pàdé àwọn tó ń gbé wọn lọ sí ilé ìwòsàn, kódà ọ̀kadà la lò láti gbé wọn.
bbc
yo
Ó kù díẹ̀ ká dé ilé ìwòsàn ni wọ́n pàdánù ẹ̀mí wọn, ojú ẹsẹ̀ tí a dé ilé ìwòsàn àwọn Dókítà tiraka láti dóòlà ẹ̀mí wọn ṣùgbọ́n ẹ̀pa kò bóró mọ́..
bbc
yo
Lára àwọn ọ̀dọ́ agbègbè gẹ́gẹ́ níbi tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti wáyé ṣàlàyé wí pé,“Pásítọ̀ Adegboyega ti ṣáájú àkókò yìí ni àríyànjiyàn ránpẹ́ pẹ̀lú àwọn Fúlàní ọ̀hún, nítorí dó wọn kò jìnnà sí ilé pásítọ̀ Adegboyega.
bbc
yo
Ó kù díẹ̀ ká dé ilé ìwòsàn ni wọ́n pàdánù ẹ̀mí wọn, ojú ẹsẹ̀ tí a dé ilé ìwòsàn àwọn Dókítà tiraka láti dóòlà ẹ̀mí wọn ṣùgbọ́n ẹ̀pa kò bóró mọ́.
bbc
yo
Lẹsẹkẹsẹ ni a kó ara wa jọ láti wá àwọn Fúlàní náà, wákàtí díẹ̀ lẹ́yìn tí à ń wá wọn káàkiri inú igbó la báwọn pàdé ṣùgbọ́n a ó rí ẹni tí ó ṣiṣẹ́ ibi náà..
bbc
yo
Lẹsẹkẹsẹ ni a kó ara wa jọ láti wá àwọn Fúlàní náà, wákàtí díẹ̀ lẹ́yìn tí à ń wá wọn káàkiri inú igbó la báwọn pàdé ṣùgbọ́n a ó rí ẹni tí ó ṣiṣẹ́ ibi náà.
bbc
yo
rẹ̀ pè é láti wá bá àwọn darandaran tó da ẹran wọn gba inú oko iṣu rẹ̀..
bbc
yo
rẹ̀ pè é láti wá bá àwọn darandaran tó da ẹran wọn gba inú oko iṣu rẹ̀.
bbc
yo
Ìgbà àkọ́kọ́ kọ́ nìyí tí pásítọ̀ ti ń pe akiyesi àwọn darandaran náà láti mú àwọn ẹran wọn gba ibòmíràn tí wọn kò sì dá pásítọ̀ Adegboyega lóhùn..
bbc
yo
Ìgbà àkọ́kọ́ kọ́ nìyí tí pásítọ̀ ti ń pe akiyesi àwọn darandaran náà láti mú àwọn ẹran wọn gba ibòmíràn tí wọn kò sì dá pásítọ̀ Adegboyega lóhùn.
bbc
yo
Ọ̀gbẹ́ni Jacob ní gbogbo ọkọ olóògbé ọ̀hún kò ju ẹ̀bẹ iṣu díẹ̀ lọ yàtọ̀ sí ibi tí ó gbin ẹ̀fọ́ àti ewédú sì lọ..
bbc
yo
Ọ̀gbẹ́ni Jacob ní gbogbo ọkọ olóògbé ọ̀hún kò ju ẹ̀bẹ iṣu díẹ̀ lọ yàtọ̀ sí ibi tí ó gbin ẹ̀fọ́ àti ewédú sì lọ.
bbc
yo
Orísun àwòrán, David of the Night/Facebook/google ìjọba Ìpínlẹ̀ Zamfara lápá gúúsù àríwá orílẹ̀èdè Nàìjíríà ti ṣàlàyé ìdí tó fi gbé àwọn ọjà tí wọ́n ti ń ta màálù tipa nipinle náà.
bbc
yo
L’Ọjọru ni ijoba kede pe oun ti ti awon oja naa ni ijoba ibile meje láwọn ibi ti ijoba ti so pe won n da màálù ti won ji gbe po mo awon ẹran bere.
bbc
yo
Komisona eto iroyin ati aṣa, manNirvana Hìdára Kaura, sọ fun BBC pe ijoba gbe igbese yii lati Dáàbò bo emi ati dukia awọn eeyan ipinlẹ naa.
bbc
yo
Ó fikùn ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé ìwádìí àwọn èso elétò abo fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé níṣe làwọn jàǹdùkú tó ń jí màálù àwọn èèyàn máa ń tàwọn ẹran náà lọ́jà láti lè máa ṣiṣẹ́ ibi wọn lọ..
bbc
yo
Ijọba Ipinle Zamfara lápá guusu ariwa orilẹede Naijiria ti ṣalaye idi to fi gbe awọn ọja ti wọn ti n ta màálù tipa nipinle naa.
bbc
yo
Ó fikùn ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé ìwádìí àwọn èso elétò abo fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé níṣe làwọn jàǹdùkú tó ń jí màálù àwọn èèyàn máa ń tàwọn ẹran náà lọ́jà láti lè máa ṣiṣẹ́ ibi wọn lọ.
bbc
yo
Káura ṣàlàyé pé òwòna ni ọ̀rọ̀ ètò abo lágbára, àmọ́, Komisona naa gbàgbọ́ pé ìgbésẹ̀ ìjọba yóo dínà máwọn jàǹdùkú ọ̀lẹ tó ń jí màálù àwọn aráàlú gbé lọ tà..
bbc
yo
Káura ṣàlàyé pé òwòna ni ọ̀rọ̀ ètò abo lágbára, àmọ́, Komisona náà gbàgbọ́ pé ìgbésẹ̀ ìjọba yóo dínà máwọn jàǹdùkú ọ̀lẹ tó ń jí màálù àwọn aráàlú gbé lọ tà.
bbc
yo
Kìí ṣe ìgbà àkọ́kọ́ rèé tí ìjọba ìpínlẹ̀ Zamfara yóò ti ọjà màálù pa torí àwọn olè ají ẹran ẹlẹ́ran ta..
bbc
yo
Kìí ṣe ìgbà àkọ́kọ́ rèé tí ìjọba ìpínlẹ̀ Zamfara yóò ti ọjà màálù pa torí àwọn olè ají ẹran ẹlẹ́ran ta.
bbc
yo
Lóṣù kẹ́sàn án tó kọjá lọ, ìjọba ti irú ọjà bẹ́ẹ̀ méje pa lórí ẹ̀sùn kàn án nígbà tí iṣẹ́ ìwádìí sì ń tẹ̀síwájú..
bbc
yo
Lóṣù kẹ́sàn án tó kọjá lọ, ìjọba ti irú ọjà bẹ́ẹ̀ méje pa lórí ẹ̀sùn kàn án nígbà tí iṣẹ́ ìwádìí sì ń tẹ̀síwájú.
bbc
yo