cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Tèmióiregẹ́gẹ́ bí ìtàn ti sọ, ẹni tí ó kọ́kọ́ tẹ̀dó sí àdúgbò yìí wá Judea ṣe àtìpó fún ìgbà díẹ̀ ni ṣùgbọ́n nígbà tí ó di wí pé ìwà ṣe dára, tí ó sì kó àwọn ènìyàn mọ́ra, ni ó bá kúkú fi ibẹ̀ ṣe le..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ àgbẹ̀ ni a gbọ́ wí pé ó ma ń ṣe, ó ń gbé ní odò òkunnn kan kí ó tó di wí pé òun náà kọ́ ilé ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Ibi tí ó wá lọ kọ́ ilé ara rẹ̀ sí ni ó pẹ́ ní tí èmi di iṣẹ́ ní ìlú pamọ́.Ìlú ọba-Iṣi-nílé-tààrà àdúgbò yìí ni wọ́n ti kọ́kọ́ kọ́ ilé pẹ̀lú búlọ́kù ní ìlú yìí, ilẹ̀ koríko ni ó pọ̀jù láyé àtijọ́..
wikipedia
yo
Bí àwọn ènìyàn bá ti wá ń sọ̀rọ̀, wọn yóò máa wí pé àwọn ń lọ sí ilẹ̀ tààrà, èyí ni ilẹ̀-gidi, tí a kù fi koríko kọ́..
wikipedia
yo
Isawọìtàn fi yé wa wí pé, Inú igbó ní àdúgbò yí tẹ́lẹ̀ kí ilẹ̀ ti dé ibẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń pe igbó yìí ní Igbó-isà ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n kọ́ ilẹ̀ ibẹ̀, wọ́n wá ń pe ibẹ̀ ní àdúgbò isàwó..
wikipedia
yo
Bákòkò ẹ̀mí tí ó tẹ̀ ágbọ́ yìí du ni wọ́n wí pé, ó wá ẹrubinrin ìlú wọn tí à ń pè ní òkú Lebgbé e ọmú-àrán..
wikipedia
yo
Ìtàn wí pé, Àdúgbò yìí ni bàbá yìí pé sí tí ó sì dàgbà kí ó tó kú..
wikipedia
yo
Nígbà tí, ó wà láyé, Bbọ̀ ni wọ́n ma ń pè é, lẹ́hìn tí ó kú tán, ni wọ́n bá ń pe àdúgbò yìí ní bábùkó..
wikipedia
yo
Ìsàlẹ̀-ọba tí wọ́n fi ń pe àdúgbò yìí bẹ́ẹ̀ ni pé, àdúgbò yìí jẹ́ ibi tí kòtò wà, ó sì tún jẹ́ wí pé, ó tẹ̀dó sí ibi àbáwọ ìlú..
wikipedia
yo
Ìdí ni yìí tẹ̀dó sí òpópó-ọ̀nà tí ó lọ sí ìlú Ìwọ-ìsìn..
wikipedia
yo
Ìmọ̀jì gẹ́gẹ́ bi ìwádìí ti mo ṣe, orí-ilẹ̀ àdúgbò yí ni wọ́n ma ń sin òkú sí láyé àtijọ́..
wikipedia
yo
Orí-ilẹ̀ yìí kò jìnnà pupọ sí ààrin ìlú kí ó tó di wí pé, ìlú fẹ́ dé ibẹ̀, ni wọ́n bá kúkú ń pè é ní àdúgbò ìmọ̀jí..
wikipedia
yo
Odò-idì ti àdúgbò yí fi ń jẹ bẹ́ẹ̀ ni pé, ó wà nítòsí odò kan tí àwọn ará ìlú fi ń fọṣọ..
wikipedia
yo
Odò yìí kò tóbi púpọ̀, kódà, ó ma ń yáw ó àdúgbò yìí ní ìgbà ọjọ́..
wikipedia
yo
ilé-ọ̀dọ̀ ni wọ́n ma ń pè é tẹ́lẹ̀ kí wọn tó sọ ọ́ di ọ̀dọ́-ilẹ̀ báyìí..
wikipedia
yo
Ìtàn wí pé, bí ojú bá ti ń ro, àgbàré òjò yíò kó ì46 játì òkè yìí lọ sí ìsàlẹ̀-ọba, àwọn ará ìsàlẹ̀-ọba yóó wá a wí pé, Agbára ọ̀rẹ́ ló kó ìdọ̀tí wá sí àdúgbò àwọn..
wikipedia
yo
Kò pẹ́ pupọ, ni wọ́n bá ń pe àwọn ará òkè yìí ní àwọn onílẹ̀ ìdọ̀tí àgbàrá-òkè..
wikipedia
yo
Agbára-òkè yìí ni wọ́n wá fi ń pe àdúgbò yìí kí ó tú di wí pé, ó ń jẹ ọ̀kẹ́-agbára tàbí òkè-àgbàálẹ̀..
wikipedia
yo
Ahabu ní orúkọ jẹ́ tẹ́lẹ̀ ṣùgbọ́n nígbà tí ó di wí pé, ẹnì kan tí ó tip ẹ̀ lẹ́nu iṣẹ́-ọba ní ìpínlẹ̀ Èkó tí ó jẹ́ ọmọ ìlú yìí kú, ni wọ́n bá ń fi orúkọ rẹ̀ pe àdúgbò yí nítorí pé, ó jẹ́ ọmọ bíbí àdúgbò yí bákan náà..
wikipedia
yo
Àwọn ará ìlú Ọba gba àwọn ẹ̀gbira jája bá wọn gbé ekùú tí wọ́n náà..
wikipedia
yo
Wọ́n wa ilẹ̀ sí ẹ̀hìn odi ìlú, wọ́n sì ń pe ibẹ̀ ní ilé-ekùú..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ní báyìí, wọ́n ti kọ́ ilé yí ni wọ́n wá ń pè ní ẹlẹ́kùú ṣùgbọ́n èyí kò túmọ̀ sí wí pé, àwọn àdúgbò yí ló ní ẹkùú náà..
wikipedia
yo
Ọ̀fẹ́-áránì kú fi ìdí mú pàtó pàtó bí àdúgbò yí ṣe jẹ́ ṣùgbọ́n ari-gbámú ìtàn kan ni wí pé, àwọn àdúgbò yí jẹ́ ìbátan kan ni wí pé, àwọn àdúgbò yí jẹ́ ìbátan kan ní ìlú ọmú-àrán nítorí pé, àdúgbò ń jẹ́ ọ̀fẹ́-aràn..
wikipedia
yo
Orúkọ tí ààdúgbò yìí ń jẹ́ tẹ́lẹ̀ ní Òkè-Ìṣọ̀lá, Àkàn wọ́n lu ma ń joba ní ìlú yìí kí ó tó di wi pé, ó di agbo ilé-olé báyìí ṣùgbọ́n nítorí pé àwọn ìkàn Òkè-Ìṣọ̀lá ti jẹ́ ẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹhin, ní àkókò tí wọ́n ń jẹ ẹ́ yìí, ni wọ́n ti ń pè wọ́n ní agbo ilé-ọba..
wikipedia
yo
Orúkọ yìí kò sì yí pada títí di òní yìí bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé, kì í ṣe àwọn nìkan ló ń jọba báyìí..
wikipedia
yo
Wọ́n wí pé, Ẹnì kan tí ó sọ wí pé, òun kò lè kọ́ ilé sí ibi tí wọ́n ń sin òkú sí ni ó sì kúrò ní àdúgbò ìmọ̀jí lọ sí ibòmíràn tí ó sì pe ibẹ̀ ní ibẹ̀ ní ibi-ìdẹ̀ra fún òun..
wikipedia
yo
Àwọn ẹyẹ wọ̀nyí a máa fò káàkiri orí igi t'ọ̀sán t'òru, bákan náà ni òkè pọ̀ sí àdúgbò tí à ń sọ nípa rẹ̀ yìí..
wikipedia
yo
Ní ìgbà tí ó ṣẹ̀, àwọn ènìyàn bẹ̀rẹ̀ sí tẹ̀dó sí àdúgbò yìí, wọ́n ń kó ilé mọ́lẹ̀ síbẹ̀ àwọn ẹyẹ wọ̀nyí kò fi àdúgbò náà sílẹ̀..
wikipedia
yo
Obinrin kan lára àwọn tí ó kọ́kọ́ tẹ ìlú náà dó tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ “bẹ́jẹ̀” akikanju obinrin ni, òun ni ó pa àwọn ẹyẹ àgbìgbò náà run..
wikipedia
yo
Wọ́n sì sọ àdúgbò náà di òkè àgbìgbò, tí wọ́n wá ń pè ní “Òkè Agbo” ní òde òní..
wikipedia
yo
Wọ́n sì máa ń kí àwọn ọmọ àdúgbò náà báyìí; “Ọmọ òkè Àgbò bẹ́jẹ̀” ìdí ni wí pé òun (bẹ́jẹ̀) ni ó pa gbogbo àwọn ẹyẹ ágbìgbò náà runYorùbá..
wikipedia
yo
Matthew Aremu Olusegun Obasanjo GCFR(; (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹta ọdún 1937) jẹ́ gbajúmọ̀ àgbà olóṣèlú, ajagun-fẹ̀yìntì àti ààrẹ àná orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Orúkọ bàbá rẹ̀ ni Amos adigun Ọbalúayé “Obasanjo" Bankole, ìyá rẹ̀ sìn ń jẹ́ Asabí.Obasanjo jẹ́ ọmọ bíbí Òwu ní ìlú Abeokuta ní Ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìyá rẹ̀ kú ní ọdún 1958, bàbá rẹ̀ sẹ́ kú bákan náà ní ọdún 1959.Igba Ewe kòkọ́ bi Olusegun Obasanjo ní ọjọ́ kaàrún, Oṣù kẹta, ọdún mẹ́tàlólwàwá (1937) fún Amos Ọbalúayé Bankole àti Àṣàbí lílù Ibogun Ọláogun..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ àkọ́bí àwọn òbí rẹ̀, wọ́n bí ọmọ mẹ́jọ tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n arabìrin kan loni tí ó kú..
wikipedia
yo
Ilé ìwé Saint David Ebenezer School ní Ibogún ni Olóyè Ọbásanjọ́ ti ka ìwà alakọbẹrẹ( Primary School Education),ní ọdún 1948..
wikipedia
yo
Olóyè Ọbásanjọ́ jẹ́ Ọ̀gágun tó tifẹ̀yìntì kúrò nínú iṣẹ́ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà àti olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni Aare ilẹ̀ Naijiria lati ọdún 1999 titi de ọdún 2007..
wikipedia
yo
Èyí ni ìgbà ìkẹ́ta tí Ọbásanjọ́ yíò jẹ́ ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó ti kọ́kọ́ jẹ́ Ààrẹ láyé ìgbà ìjọba ológun láàrín ọdún 1976 sí 1979.Ìfẹ̀yìntì rẹ̀lẹ́yìn tí ó fẹ̀yìntì, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àdáṣe tirẹ̀, ìyẹn ni iṣẹ́ àgbẹ̀..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ agbe rẹ̀, (Obasanjo Farms) gbooro; tó fẹ́rẹ̀ ma sí abala ise agbe tí kò sí níbẹ̀..
wikipedia
yo
Láàrín ọdún 1976 sí 1999, Ọbásanjọ́ di ẹni mímọ́ ní gbogbo àgbáyé..
wikipedia
yo
Ó wà nínú àwọn ìgbìmọ̀ tó ń pẹ̀tù sí aáwọ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè tó ń jagun, pàápàá ní ilẹ̀ adúláwọ̀..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ògúnná gbòǹgbò ninu ẹgbẹ́ kan tó kórìíra ìwà ìbàjẹ́, ìyẹn ni Transparency International..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1999, Ọbásanjọ́ tún di Ààrẹ alágbádá fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ PDP..
wikipedia
yo
A Tún Fi Ibo Yàn Án Padà Gẹ́gẹ́ Bí Àárẹ̀ Kejìkejì ní 2003...
wikipedia
yo
Ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn àfojúsùn ìjọba Ọbásanjọ́ ní ìgbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá (anti-corruption)..
wikipedia
yo
Ọbásanjọ́ gbìyànjú dídá ògo Nàìjíríà padà láàrín àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ ní àgbáyé (Committee of Nations)..
wikipedia
yo
Ó tún iyì owó náírà tó ti di abúrún bí omi gàárì ṣe, gbídókítà-lórí-ọjà (inflation) sì dínkù jọjọ..
wikipedia
yo
Iye owó afi-sókè-òkun (External rẹ̀serves) Nàìjíríà ti ga gan-an ni, ó tó $40 billion báyìí..
wikipedia
yo
Ọbásanjọ́ tún fìdí àwọn báńkì wa múlẹ̀ gbogbo, pípọ̀ tí wọ́n pọ̀ yanturu tẹ́lẹ̀ ti dínkù, wọn ò ju mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n lọ mọ́ báyìí..
wikipedia
yo
Eyi mu ki àwọn èniyàn ni igbẹkẹle ninú fifi owó pamọ́ si banki, wọ́n si tun lè yá owó fun ìdàgbàsókè okòwò wọn gbogbo..
wikipedia
yo
Lára àwọn ètò tí ìjọba Ọbásanjọ́ ń ṣe ni títa àwọn ogun ìjọba fún àwọn alàdáni (Privatisation policy)..
wikipedia
yo
Ìdí ni pé àwọn olówó ló lè ra àwọn ògùn bẹ́ẹ̀, tátilẹ̀jẹ́kà kankan kò le rà wọ́n.Ní oṣù kẹjọ ọdún 2021, ẹgbẹ́ Afirika yan Olusegun Obasanjo gẹ́gẹ́bí aṣojú gíga fún àlàáfíà ní ìwọ̀ Áfíríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn Ààrẹ ilẹ̀ Nàìià àjápọ̀ (Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wá di wí pé àwọọ́n ènìyàn ń gbé Abbẹ́gbẹ́ yìí bí ìlú ni wọ́n bá ń sọ wí pé a tún ní ní ìkén Nee o..
wikipedia
yo
Èyí mú kí ó bínú pa ìyàwó rẹ̀ àti ẹrúbìnrin náà nígbà tí wọ́n sì bí i ìdí tí ó fi ṣe bẹ́ẹ̀ ó ṣàlàyé pé n ṣe ni ẹrú yìí sanyìn-dò..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di wí pé gbogbo ènìyàn bẹ̀rẹ̀ sí fi oúnjẹ ìyá yìí júwe àdúgbò náà ni wọ́n kúkú wá ń pe àdúgbò yìí ní ajítáádún (ají-ta-dídùn)..
wikipedia
yo
Wọ́n sì sọ àdúgbò náà di òkè àgbìgbò, tí wọ́n wá ń pè ní “òkè agbo” ní òde òní..
wikipedia
yo
Ní gba tí wọ́n wá bẹ̀rẹ̀ sí tẹ ibẹ̀ dó, àwọn àgbà wá sọ orúkọ àdúgbò ní “Pà” oríkì “Já à kó obì ṣe Esa, a kérọgbọ bo ojú ogun..
wikipedia
yo
káwí káfo, àwọn ará íjí bẹ̀rẹ̀ sí ní pa àẹ̀ nínú Odò náà..
wikipedia
yo
Wọ́n a sì máa pe àwọn tí wọ́n wá láti àdúgbò yìí ní “Ọmọ Idosa máyé”
wikipedia
yo
Bí ẹnìkan báni àlejò tí ó wá a wá, wọn á ní kí wọ́n lọ wòó ní abẹ́ igi ìgbà gbóríyìn- ìgbà tí wọn kò tíì ré kúrò lórí igi..
wikipedia
yo
Ó sì jẹ́ ibi tí àwọn alágbẹ̀dẹ pọ̀ sí, bí àwọn ènìyàn bá sì fẹ́ júwe àdúgbò láti agbo ilé yìí, wọ́n á ní ẹ lọ sí ígbé alágbẹ̀dẹ, tí ó sì di ílágbede di òní yìí..
wikipedia
yo
tí ṣìgìdì bá padà dé, wọ́n á sì ṣe ètùtù, wọ́n á fún-un ní epo mu..
wikipedia
yo
Àwọn eniyan a sì máa jẹ ọ̀rọ̀ yìí, ìmọ̀ ni agbègbè ibi tí ọ̀rọ̀ yìí ń sọ sì jìngbìnnì..
wikipedia
yo
Àwọn eniyan wá sọ àdúgbò náà di ìmọ̀ ọ̀rọ̀ ìmọ̀ró ni wọ́n ń pe ibẹ̀ lóní yìí..
wikipedia
yo
Odò ńlá kan sì wà ní orí òkè ibi tí ẹ̀fọn yìí máa n lúgọ sí..
wikipedia
yo
Bí àwọn eniyan bá ń darí bọ̀ láti ọkọ̀ wọn máa ń bu omi mu ninu odò yìí..
wikipedia
yo
Tí ẹnikẹ́ni bá ṣe ohun míràn yàtọ̀ sí mímu nínú omi náà, ẹ̀fọn yóò fi imú onítọ̀hún fọn fẹ́ẹ́rẹ́..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n tí ẹfọ̀n wáá bá ti rí wí pé wọ́n ń mu omi ni, kì yóò ṣe ohunkóhun fún irú ẹni bẹ́ẹ̀, wọn yóò sì la ọmú náà dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè wí pé àwọn gun òkè ẹ̀fọn, àti wí pé omi tí àwọn mu nínú odò tí rẹ̀ ẹfọ̀n tẹ́ láti má ṣe ìjàmbá títí àwọn fi gun òkè..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ wí pé odò ńlá kan wà ní àdúgbò yìí tí ìkókó (ládugbó) àbáláyé kan wà nínú rẹ̀..
wikipedia
yo
tí àwọn ènìyàn bá fẹ́ pọn omi mumú, nínú ládugbó yìí ni wọ́n ti máa ń pọ́n-ọn..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n bí ó bá jẹ́ kí a fọ aṣọ, ìwé àti ohun míràn ni wọ́n a lo omi tí ó yí làdígbo náà ká a..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ṣe wọ́n ṣe àdúgbò náà di “Odò-o-ládugbó” tí àgékúrú rẹ̀ wá dì làgu..
wikipedia
yo
Ó ní àgbàlá ńlá tí ó máa ń da ẹran sí láti jẹ pápá, kò sí ohun ọ̀sìn míràn tí ó ń bá àwọn màlúù náà gbé ní àgbàlá náà..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ wí pé ẹ̀yìn odi ìlú ni ibẹ̀ jẹ́, wọ́n tún máa ń da àwọn àkúfọ́ ìgò jọ síbẹ̀, àwọn tí ó bá jẹ lọdú, wọn a fọ́ wọn sí wẹ́wẹ́..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ó ṣẹ̀, àwọn ènìyàn bẹ̀rẹ̀ sí tẹ̀dó sí àdúgbò yìí..
wikipedia
yo
Àwọn eniyan a máa sinmi lábẹ́ àwọn igi náà bí wọ́n bá ń ti ọ̀nà oko tabi odò bọ̀..
wikipedia
yo
Ìgbà tí ó ṣẹ̀, igbó náà bẹ̀rẹ̀ sí súnmọ́ abúlé, nítorí àwọn ènìyàn ń tẹ̀dó sí etí bẹ̀..
wikipedia
yo
Tí àwọn àgbàlagbà ní abúlé pàápàá àwọn ọkunrin bá jẹun tán wọn á “tàtaré”sí abẹ́ igi yìí láti lọ gba atẹ́gùn, ibi tí wọ́n bá ti ń tayọ, tí wọn ń “Ta sọ” wọn á wà níbẹ̀ fún ìgbà pípẹ́..
wikipedia
yo
Ẹnikẹ́ni tí ó bá ní àlejò, wọn á ní kí ó lọ wo ẹni ni ó ń béèrè ní ìdí igi ìsìn tí ó wá di “Ìdí ìsìn” lónìí..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn oníṣòwò kókó patapata ni wọ́n máa ń pàdé ní àdúgbò tí à ń ṣọ́ yìí láti wá rà ati ta kókó wọn níbẹ̀..
wikipedia
yo
Tí wọ́n bá mú ẹnikệni ti o ni oso tàbí ajé ibi tí wọ́n ti yàn lọ́pọ̀, tí wọ́n ti ń so ọkọ̀ pa wọ́n ni wọ́n ń pè ní òkè tí oso pàpọ̀ Emir e sí, tàbí òkè tiè òso oso pín sí..
wikipedia
yo
Ní ìgbà tí ó ṣe àwọn àgbààgbà tí wọ́n kú ní ìlú náà fi orí kan orí wọn sì tọ “Ifá” lọ láti bèèrè ohun tí wọ́n tẹ̀ ṣe ti agbègbè àwọn kò fín i parun lọ́wọ́ àwọn tí ó ń kó wọn lẹ́rú..
wikipedia
yo
Ifá ni ki wọn bọ odò ti ó na ni ilú wọn, ki wọn si maa pọn omi odò naa si ilé, gbàrà ti wọ́n bá gbọ́ wi pé ogun wọ̀lú, ki onikálukú bu omi naa mu..
wikipedia
yo
Láìpẹ́ ogun míràn wọlé tọ̀ wọ́n, wọ́n ṣe bí ìfà ti wí, wọ́n jagun wọ́n sì ṣẹ́gun..
wikipedia
yo
àwọn jagunjagun ìlú ní ibi tí wọ́n ti máa ń pàdé dira ogun tí wọ́n bá fẹ́ lọ sí ojú ogun..
wikipedia
yo
Àkókò tí wọ́n bá fẹ́ lọ jagun nìkan ni wọ́n máa ń pàdé ní ibẹ̀..
wikipedia
yo
Ti àwọn ènìyàn tí kò mọ ohun tí ó n ṣẹlẹ̀ tẹ́lẹ̀ bá ti ń rí àwọn jagunjagun tí wọ́n ń dé sí ìkìn yìí, wọ́n á ní àwọn ológun ti dé sí ikìn wọ́n..
wikipedia
yo
Wọ́n wá sọ ibẹ̀ di “ìtún ológun” tí àrun rẹ̀ wá di “ìtúní lógún” 🙂
wikipedia
yo
Àwọn àgbàgbà a máa jókòó ta ayọ̀ ní abẹ́ àwọn igi yìí, wọ́n a sì máa fi èso oyin panu bí ayọ̀ bá ń lọ lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Báyìí ni wọ́n sọ ibẹ̀ di “Odò tí ó ń so èso oyin” tí ó wá di “ọ̀dọ́ aṣọyín..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n, gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ wí pé àwọn Yorùbá máa ń yẹ IPún tàbí ayamọ wo (orí)..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn àdúgbò náà á dá òbí wọn á wí pé “Orí ìwọ lo mo olùsìn, olùṣerere, jẹ́ kí ìgbésí ayé mi dára o..
wikipedia
yo
Báyìí ni ẹni tí ó kọ́kọ́ jẹ ọba ìlú náà wí pé òun ni olórí ìlú, òun ni orí fún àwọn ènìyàn tí ó wà ní ìlú gbogbo ènìyàn yóò sì ma pé sin òun ni..
wikipedia
yo
Ní ìgbà míràn tí kinní ọ̀hún bá wọ̀ ọ́ lára tán, á bẹ̀rẹ̀ sí yá èèpo igi á máa rún-un wómúwómú; àwọn ẹ̀rọ tí ó ń lọ, tó ń bọ̀ lọ́nà oko máa ń wòó tàánú-tàánú; nígbà tí ó yá kò jọ wọ́n lójú mọ́..
wikipedia
yo
Wọ́n wá ń pè é ní wéré tí ó ń bó igi jẹ́, òun a sì máa lé wọn bí wọ́n bá ti pè é bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Orí òkè ńlá kan ni wọ́n sì ti máa ń pa idán oríṣiríṣi fún àwọn ará ìlú..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ṣe àwọn ènìyàn kọ́lé sí orí òkè yìí, wọ́n sì sọ àdúgbò náà di “Orí òkè idán pípa” tó wá di òkè idán” lónìí..
wikipedia
yo