cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Nígbà tí ó sọ àwọn ènìyàn fẹ́ràn láti máa ṣe ayẹyẹ oríṣiríṣi ní iwájú ìta ààfin ọba nítorí pé ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ ṣe ayẹyẹ tí ọba bat í gbọ́ nípa rẹ̀ ni yóò rí ẹ̀bùn gbà lọ́wọ́ ọba..
wikipedia
yo
Báyìí ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí lọ ìta ọba fún ayẹyẹ, bí wọ́n bá sì fẹ́ ṣe àpèjúwe ibi tí wọ́n yóò ti ṣe ayẹyẹ fún àwọn ará, ọ̀rẹ́, àti ojúlùmọ̀, wọn á ní kí wọ́n wá bá wọn ṣe ayẹyẹ ní iwájú ìta ọba..
wikipedia
yo
Níbo ni ẹ ó ti ṣe ayẹyẹ? “Ìwátà ọba ní” kẹ̀rẹ̀kẹ̀rẹ̀ wọn sọ àdúgbò náà di “Ìwátà”
wikipedia
yo
tí ètò fífi ọba jẹ yìí bá takókó tí ó dijú tán pátá, àwọn àgbààgbà afọbajẹ á kó ara wọn lọ sí orí òkè kan láti lọ tú gbogbo ohun tí ó bá díjú palẹ̀..
wikipedia
yo
Ní orí òkè yìí wọ́n á dìbò, wọn á dá ìfà, ohun gbogbo yóò sì ní ojútùú kí wọ́n tó padà sí ilẹ̀..
wikipedia
yo
Nítorí ìdí èyí ni wọ́n ṣe sọ òkè náà di “Òkè tako” òkè tí a ti ń tú ohun lérò tí ó ta kókó..
wikipedia
yo
Orí òkè yìí ni ó di àdúgbò ńlá loni, tí wọ́n sọ di “Òkè Alaafia”
wikipedia
yo
ní gba tí ó ṣe ọba ṣe akiyesi wí pé gbogbo àwọn àlejò wọnyi ń ṣe bí ọmọ ìyá kan náà, a fi bí ẹni pé ilẹ̀ kan ni gbogbo wọn ti wá..
wikipedia
yo
Láì fa ọ̀rọ̀ gùn, àwọn àlejò yìí ń pọ̀ sí, wọ́n ń bí sí i, wọ́n ń ré sí, ìlú sì kún tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí onílé kò mọ àlejò mọ́..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kan, Ob apẹ gbogbo àwọn àlejò ìlú jó tẹbí tará,àwọn ó sì sọ fún wọn wí pé òun ríi pé wọ́n ní ìfẹ́ ara wọn, láti òní lọ, òun (ọba) yán-ń-dá orí òkè tí wọ́n ti búra ní ọjọ́sí fún wọn, kí wọ́n kọ́ àwọn ènìyàn wọn kí wọ́n lọ tẹ̀dó sí ibẹ̀..
wikipedia
yo
Láti ìgbà náà ni wọ́n ti sọ àdúgbò náà di orí òkè ìfẹ́ tí ó di “Òkè ìfẹ́” lóní yìí..
wikipedia
yo
Bàbá kan wà tí ó jẹ́ ògbóǹtagí oníṣègùn; ìkọ́ ni ó máa ń fi ríran sí àwọn ènìyàn..
wikipedia
yo
Ohun kóhun tí eniyan bá bá lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ ikọ̀ yìí ni ó máa kọ kalẹ̀ tí yóo sì máa bá sọ̀rọ̀ bí eniyan; ṣugbọn ohùn nìkan ni ó máa ń gbọ́ èdè tí ikọ̀ náà ń sọ, òun yóo wá túmọ̀ fún ẹni tí ó wá ṣe àyẹ̀wò..
wikipedia
yo
Ní ìdí èyí, wọ́n sọ “Baba’yìí ní “àti ikọ̀ rí ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ sí ènìyàn” tí ó di “àti’ nígbà tí àwọn ènìyàn tẹ̀dó sí àdúgbò náà..
wikipedia
yo
Orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ “Ọmọdorí” ò ṣe iṣẹ́ takun-takun fún ìlú baba rẹ, ó sì jẹ́ ọmọ ọba”..
wikipedia
yo
Ní ìgbà tí ọba tó wà lórí oyè wàjà, ìdílé rẹ̀ ni ọba kan òun sì ni ó yẹ ki wọn mú, ninú idilé náà..
wikipedia
yo
Àwọn afọbajẹ gba abẹ́tete lọ́wọ́ ẹlòmíràn wọ́n sì kojú “Arádorí” sọÒru àlè..
wikipedia
yo
Kàkà kí ilẹ̀ kú, ilẹ̀ á ṣá ní ọmọderíoyè fi ọ̀rọ̀ náà ṣe ati bí a ṣe mọ̀ wí pé àwọn alágbára kò kọ ikú ọmọdorí ṣe ọkunrin, ó sì pinnu wí pé bí wọn kò tilẹ̀ fi òun jọba wọn kò ní gbàgbé òun láyéláyé..
wikipedia
yo
Báyìí ni “Ọmọdorí tí àwọn ènìyàn ti ṣe àgérí orúkọ rẹ̀ sì “Momówó” tẹ́lẹ̀, di odò ńlá kan sí odi ìlú náà, ó sì fi ohùn sílẹ̀ wí pé, ọba tí ó bá jẹ tí kò bá mu nínú omi náà kí ni pé lórí oyè tí wọ́n fi jẹ, àti wí pé ẹnikẹ́ni tí ó bá ń mu omi náà yóò di alágbára..
wikipedia
yo
Bíi àwọn ènìyàn ṣe bẹ̀rẹ̀ sí ní tẹ̀dó sí etí odò náà ni yìí, tí wọ́n sì sọ àdúgbò náà ti “Tìbroye” ìyàn niyà ẹ “ọ̀dọ̀ ọmọ oyè”
wikipedia
yo
Ibẹ̀ ni wọ́n ń pè ní Station, Ibikiri tí ènìyàn bá ń lọ láti Ìjẹ̀bú Igbó, ibẹ̀ nìkan ni ẹ ti lè ri ọkọ̀ wọ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí oníṣẹ́ yóó jíṣẹ́ fún ọba ohun tí o kò sọ ní pe àkún mi èyí tí ó túmọ̀ Psí e àkún ni àdàpè ayára ṣùgbọ́n nígbà tí ìṣẹ̀lẹ̀ yí mi gbogbo Akingbà ni wọ́n fi ń sọ pé àkún mi tí wọ́n sì wáá sọ àdúgbò náà ní Bkúnkún láti ìgbà náà ni wọ́n ti ń jẹ olóye tí a ń pè ní alákún..
wikipedia
yo
Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ẹ́ lọ sí àdúgbò yí wọn a ní ó lo òkè olè..
wikipedia
yo
Èdè adùgba ni àkúwa èyí tí ó túmọ̀ sí pé ìwà nìkan ni ó kù wọ́n kú..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ ni àwọn ènìyàn sì gbàgbọ́ pé adù ti sé wa ibẹ̀ ni olóye àkọ́kọ́ ti jẹ́..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pè é ní ubẹ̀rẹ̀-ibi tí nǹkan ti bẹ̀rẹ̀ tabi ṣẹ..
wikipedia
yo
Gbogbo ilẹ̀ tí ó wà ní àdúgbò yí ni wọ́n sì ń pè ní òdodo èyí tí ó túmọ̀ sí òde (ilé)- ọdẹ-odè tasí òdodo..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń péa wọ́n tó létò láti táì lé tabi láti pín ilẹ̀ ní egbò tí àdúgbò wọn sì ń jẹ ọ̀lalé..
wikipedia
yo
Ní àdúgbò bí ni wọ́n sit í ń jẹ ọba títí jí oní-oloni èyí wá wà ní ìbámu Pẹ́là ọ̀rọ̀ Yorùbá tó sọ pé ọba ló nílé..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n bi baba yí léèrè èrèdí tó fi ń lu ìlù ó ní ó ń mú òun láradá ni..
wikipedia
yo
Àgbàdo yìí ni wọ́n ń pè ní egbò tí wọ́n sì ń pe odò yìí ní odò-egbò tí wọ́n sì so àdúgbò yín i ọdẹegbò..
wikipedia
yo
Ọ̀nà tí ó wà ní ẹsẹ̀ òkè yí ni ẹni tí ó tẹ̀ ẹ́ dó ń gbé ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pe àdúgbò yí ní ọ̀nàke..
wikipedia
yo
Ó sọ fún àwọn ará ìlú rẹ̀ ní ọjọ́ kan wí pé tí wọ́n bá náà ọjà ṣùgbọ́n wòk ó, ọba pàṣẹ kí wọ́n lọ jẹ ọjà náà run..
wikipedia
yo
Bèèrè ni wọ́n máa ń pe ẹ̀gbọ́n ní tiwọn gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà ní àwọn ìlú tabi agbègbè kọ̀ọ̀kan lóde òní, tí ọkunrin náà sì máa ń sọ fún ọpọlọpọ eniyan pé ibí yìí ló yẹ kí bèèrè òun dó sí, ṣugbọn tí kò dó sibẹ, òun yóo wá máa pe ibí yìí ní “Ibi ti bèèrè kò dó sí” tí wọn ń dá pè ní ìbẹ̀rẹ̀ báyìí..
wikipedia
yo
Ní torí pé ibi yìí ni wọ́n ti ń bọ òrìṣà yìí ni wọ́n ṣe n pè é ní ìta oṣù..
wikipedia
yo
Wọ́n sì máa ń ná ọjà ní àdúgbò yìí títí di òní yìí ..
wikipedia
yo
Níbẹ̀ ni ilé ìpàdé wọn wà, kí ó tó di pé wọ́n tẹ ibẹ̀ dó..
wikipedia
yo
Oríta tí wọ́n ń náà yìí ni ó di àdúgbò, tí wọ́n sì ń pè ní ìta ọ̀pọ̀..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ fún wa pé apá àṣẹ Ọba ìlú ibòbí lọ mú ṣdani nígbà tí ó ń bó, àwọn kan tilẹ̀ sọ pé àrẹ̀mọ Ọba ìlú náà ni..
wikipedia
yo
Ọkùnrin akọni tí a ń pè ní ọ̀rọ̀ ni ó pe ọ̀fọ̀ tí ó sì lé omi náà lọ..
wikipedia
yo
Nígbà tí ìjà dé láàrin òun àti àwọn tí wọ́n fọ́ wọ ìlú yìí, ó bínú padà sí ibí yìí ó sì wọlé..
wikipedia
yo
Eégún ọdọọdún ni eégún máa ń jáde ní àdúgbò yìí títí dónìí..
wikipedia
yo
Ìdí igi ìrókò ni wọ́n fi ṣe ojúbọ eégún yìí igi ìrókò yìí wà níbẹ̀ títí dòní yìí..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn kò ṣe iṣẹ́ epo níbẹ̀ mọ́, wọ́n sì ń ná ọjà epo níbẹ̀ títí dó níí..
wikipedia
yo
Ìdí nì yìí tí a fi máa ń yan ọba láti ìdílé ẹnití ó tẹ àdúgbò náà dó..
wikipedia
yo
Ìdílé yìí náà tilẹ̀ ní àáfún tí à ń pè ní ààfin ọba idẹwọ́n..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n lọ bí ìfà wó, Ifá ni kí wọ́n máa bọ Ọbàtálá ní ìdílé náà, láti ìgbà náà lọ ni wọ́n ti ń bọ Ọbàtálá ní ìdílé yìí..
wikipedia
yo
Tí ó bad i àsìkò ọdún oriṣa yìí, àríyá ni fún gbogbo àwọn ọmọ àdúgbò yìí ati fún ìlú pàápàá..
wikipedia
yo
Onanuga (1981), ‘Ilu Ijebu-Ode', lati inu 'Ọdun oriṣa Agẹmọ ni agbegbe Ijebu-Odeèdè apileko fun oye BiEE, Dall..
wikipedia
yo
OAU, Ifẹ̀, Nigeria, ojú-ìwé 3–ìtàn Ìjẹ̀bú-Òde/oríṣìíríṣìí ni ìtàn tí à n gbọ́ nípa ìṣẹ̀dá Ìjẹ̀bú òde..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n èyí tí ó wọ́ pọ̀ jù nínú àwọn ìtàn náà ni mo mẹ́nu bà yìí; aláDuigbó ni Odùduwà àti aláre jẹ́ ní apá ilẹ̀ Lárúbáwá..
wikipedia
yo
Odùduwà ni a gbọ́ pe ó kọ́kọ́ sí kúrò ní agbègbè náà wá sí Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn rẹ̀ ni aláre kúrò ní ilẹ̀ wadáì; tí ó gba aṣálẹ̀ Núbíà dé ilé-ìfẹ́, tí ó sì ṣe “Ẹ-ǹlẹ́-ń bẹ̀un O” fún Odùduwà..
wikipedia
yo
Aláré fi ọmọbìnrin rẹ̀ kan gborowó, fún Odùduwà láti fi ṣe aya..
wikipedia
yo
Lẹhin eyi, ó gba ọ̀nà iṣẹ́ri dé ibẹ̀ṣe, titi ó fi dúró ni Ìjẹ̀bú-Òde..
wikipedia
yo
Fún iṣẹ́ ribiribi wọn fún ìlú ni a ṣe sọ ibùdó náà lórúkọ wọn - ajẹbu-ọlọ́dẹ..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn aláre ní lúwa (Olú-ìwà) náà dé láti aṣálẹ̀ Núbíà..
wikipedia
yo
Èdè àìyedè bẹ́ sílẹ̀ láàárín aláre àti lúwa lórí, i ẹni tí yóò jẹ ọlọ́jà..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n tọ Ifá lọ lórí ọ̀rọ̀ yìí, ó fi yé wọn pé ẹni tí yóò jẹ́ olórí kòì tíì dé!
wikipedia
yo
Kò pẹ́ kò jìnnà, lẹ́hìn ikú aláre àti lúwa, ni àjèjì kan tí ó múra pápá-rere wọ̀lú..
wikipedia
yo
Kò pẹ́, ìròhìn ti tán ká pé ajíjí kan fẹ́ gbógun wọ̀lú..
wikipedia
yo
Èyí ni ó mú apẹbí (olóyè pàtàkì kan ní ibùdó yìí) ló bàá bóyá ìjà ni ó bá wà ní tòótọ́..
wikipedia
yo
Àjèjì yìí kò fèsì ló baà bóyá ìjà ni ó bá wà ní tòótọ́..
wikipedia
yo
Àjèjì náà fi yé wọn pé ògbógangan-ajogún ni orúkọ òun..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ gborowọ́ tí í ṣe ọmọbìnrin aláre tí ó fún Odùduwà fẹ́ ní Ilé-Ifẹ̀, ipasẹ̀ àwọn ẹbí ìyáa rẹ̀ ní ògbórógannda tó wà, lẹ́hìn ikú bàbá rẹ̀..
wikipedia
yo
Títí di òní, àdúgbò tí àpèbí ti pàdé ògbórogannda ni à n pè ni ijada..
wikipedia
yo
Apábi lo fi tọ Oloye agba JáIGIG tí o rán an níṣẹ́ pé ọwọ́ èrò ní àjèjì náà mú wá..
wikipedia
yo
Nígbà tí jáIGIG bí àpébí ibi ti àjèjì náà wà, àpébí dáhùn pé “ọba-nnì” (ọba wa ní ìta) nítorí ipò ọba ní ó rí i pé ó yẹ ẹni pàtàkì bí i tí ìfihàngband-kọ́-ajogún..
wikipedia
yo
Láti ìgbà yìí ni a ti mọ ogbórogannda ni Obanta, ti Ajápe rẹ di obàǹtà di oni..
wikipedia
yo
Agbegbe ti Gobamu ti le Osa lo ti a fun Osungannda lati maa gbe ni o juwe pe" o too ro"- (ibi yìí) to lati duro si) ni a n pe ní itoọrọ di oni..
wikipedia
yo
Àdúgbò yìí ni a ṣe ọ̀wọ́n kan sí ní ìrántí óbàǹtà, nítorí a kò mọ bí ó ṣe kú..
wikipedia
yo
ọ̀gbọ̀rọgbannda ajogún (obàǹtà) gbé wínniadé, ọmọ òsì níyàwó..
wikipedia
yo
Síbẹ̀ aáwọ̀ tí ó wà láàárín lúwa àti aláre nípa òye jíjẹ kò í tán láàárín àwọn ẹbí méjèèjì..
wikipedia
yo
Láti fi òpin sí aáwọ̀ yìí, àwọn ará ìlú ni kí mọ́niwa, ọmọ òbàǹtàbanta, jáde rẹ̀ ti ṣe ní ọjọ́ kìíní..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ìletò kan tí a mọ̀ sí ọ̀dọ́, láti ibẹ̀ ni ó sì ti padà wọ ìlú pẹ̀lú ifọ̀n àti orin..
wikipedia
yo
Oun ni o jẹ ẹni akọkọ ti o jẹ oye Awujale - 'A-mu-ija-ile/eyi ni eni ti o pari ija ti o ba nílé..
wikipedia
yo
Títí di òní yìí ni ẹnikẹ́ni tí a bá yàn gẹ́gẹ́ bí ọba tuntun gbọ́dọ̀ jáde ní ìlú lọ sí ọ̀dọ̀, kí ó sì wọ ìlú padà gẹ́gẹ́ bí i mọ́niwawá àti ọbàǹtà kí ó tọ́ ó gbadé..
wikipedia
yo
Lára àwọn Olóyè pàtàki-pàtàki ni Ìjẹ̀bú-Òde ni Olisa egbò, àgbọn, kakanfo, jáIGji àti lápò, ti wọn jẹ oyè ìdílé..
wikipedia
yo
Awùjalẹ̀ kọkànléláàádọ́ta ni a gbọ́ pé ó wà lórí oyè báyìí..
wikipedia
yo
Wọ́n tún fẹ́ràn láti máa fi ògiri sí ọbẹ̀ àti oúnjẹ wọn mìíràn bíi ìkọ́kọrẹ́ láti fún ún ní adùn ajẹ́pọnẹlẹ́ṣin..
wikipedia
yo
ẹ̀sìn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ ní àwọn ènìyàn Ìjẹ̀bú òde ní ìgbà làìtọkàn..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń bọ oríṣìíríṣìí òrìṣà tí a ń bọ ní gbogbo ilẹ̀ Yorùbá bí i ogún, ìfà, Èṣù àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àwọn òrìṣà ìbílẹ̀ bíi agẹmọ, ọ̀rọ̀, àti obìnrin-òjòwú wà pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Lóde òní àwọn ẹṣin ìbílẹ̀ wọ̀nyí kò ranlẹ̀ bíi ti àtijọ́, síbẹ̀ a sì ń bọ́ wọn lójú méjèèjì..
wikipedia
yo
ẹ̀sin ṣumàáluni ni ọ̀pọ̀ àwọn ará Ìjẹ̀bú-Òde ń ṣe báyìí..
wikipedia
yo
Mọ́ṣáláṣí kan wà ní àdúgbò Igbogbo tí ó jẹ́ ọ̀kan nínu mọ́sálásí tí ó tóbi jù ní apá ìwọ̀ oòrùn Áfríkà..
wikipedia
yo
Àwọn ẹlẹ́ṣin atẹle Kristi lóríṣìíríṣìí kọ gbẹ̀hìn..
wikipedia
yo
Ìtàn sọ fún wa pé apá àṣẹ Ọba ìlú ibòbí lo mú ṣdani nígbà tí ó ń bó, àwọn kan tilẹ̀ sọ pé àrẹ̀mọ Ọba ìlú náà ni..
wikipedia
yo
Nígbà tí ìjà dé láàrin òun ati àwọn tí wọ́n fọ́ wọ ìlú yìí, ó bínú pada sí ibí yìí ó sì wọlé..
wikipedia
yo
Nígbà tó di ọjọ́ kún, àwọn ọmọdé tó ń dẹ̀gbẹ́ bá ṣèèṣì finá sí oko..
wikipedia
yo
Ẹnìkan sáré Wade sáàrin ìlú láti sọ fún wọn pé odi ìlú ti ń jóná..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ ni àwọn omibodè máa ń dúró sí láti máa ṣọ́ ìlú náà..
wikipedia
yo
Ojúbọ odò náà ni wọ́n fi sọ àdúgbò ibẹ̀ ní orúkọ tó ń jẹ́ láti máa fi ṣe ìrántí rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pe odò náà ní orúkọ rẹ̀ Ògùnpa, tí orúkọ náà sì di orúkọ àdúgbò náà..
wikipedia
yo
Ìdí sì nìyí tí wọ́n fi ń pe àdúgbò náà ní orúkọ yìí..
wikipedia
yo
Àdúgbò yìí ni wọ́n kọ́kọ́ kọ́ ilé oní bíríkì sí ní ìlú Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Ati pé ibẹ̀ ni wọ́n ti máa ń ṣe àṣeyẹ fún ẹni tó bá kú tí kìí ṣe ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí tàbí ìgbàgbọ́..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí wọ́n fi sọ odò náà ní kúde tí láti máa fi ṣe ìrántí akọni náà, tí gbogbo agbègbè náà sì dì kú bákan náà..
wikipedia
yo
Agbègbè tí ilé ẹni ti máa ń gbé eégún náà wà ni à n pè ní ọdẹ-ajé Olóolu sì ni orúkọ egungun náà ní òde-ajé-olóòtú..
wikipedia
yo
Gbogbo ìgbà tí ó bá fi ń fún àwọn ń nkan ọ̀sìn rẹ̀ lóńjẹ, ni òun náà máa ń jẹ àgbàdo tí rẹ̀..
wikipedia
yo