cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Owó àtijọ́ ati tuntun jọra pẹlu àwòrán Oloye Obafemi Awolowo to wa niwaju rẹ, atunṣe to ko wa nibe ni awọ ti wọn paarọ, ati akosile “one Nigeria, great Promise” | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ọwọ́ tuntun náà ó ní kíní kékeré kan tí ènìyàn le Kakáání tí a sì gbé wá lọ sí àyọkà tí wọ́n kọ lórí ìtàn Nàìjíríà.Ní ọdún 2019, N100 gba àbùdá àdámọ̀ tuntun nígbà tí ìbòwówe Priscilla Ekwere ẹlẹ́jẹ̀, tó jẹ́ Director of Curdi operations fún Central Bank of Nigeria, tó sì tún jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ tó máa kọ́kọ́ wà nípò náà.Ọ̀wọ́n gógó náírà ní ọdún 2023 lẹ́yìn ìgbà tí báńkì àpapọ̀ yí àwọ̀ owó náírà ìgbà(N200), ẹẹdẹgbẹtan500n) àti ẹgbẹ̀rún(1000) pọ̀, owó náírà ti ṣọ̀wọ́n.Àwọn ìtọ́kasí Naijirisùúrù orúkọ-owó.. | wikipedia | yo |
(Ọjọ́-ìbí rẹ̀ ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹjọ ọdún 1961) jẹ́ olóṣèlú àti Ààrẹ orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀.. | wikipedia | yo |
O jẹ oloselu orile ede Amerika, omo ile igbimo asofin lati ipinle Illinois, omo egbe oselu Democrat.. | wikipedia | yo |
Barack Obama jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn òṣèlú meji tí wọ́n figagbága láti jẹ́ ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kẹrin oṣù kọkànlá ọdún 2008 Obama wọlé ìbò fún ipò ààrẹ ilẹ̀ Amẹrika.. | wikipedia | yo |
Barack Obama jẹ́ aláwọ̀ dúdú àkọ́kọ́ ti ọ̀kan ninu àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú nlá ti ilẹ̀ Amẹrika fun ni anfani lati kópa ninu eré ìje àti di ààrẹ ilẹ̀ Amẹrika lati ẹgbẹ́ òṣèlú Democrat.Ìgbésí ayé wọn bi Barack Obama ní ìlú Honolulu, ìpínlẹ̀ Hawaii ní ọdún 1961.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí rẹ̀ rí ara wọn ní ìgbà tí wọ́n ńká ìwé ní ilé ẹ̀kọ́ Unifasiti Hawaii ní ìlú Manoa.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ wá láti orílẹ̀ èdè Kenya.Barack Hussein Obama- àgbà, lọ ka ìwé nípa ọrọ̀ ajé ní ilẹ̀ Amẹrika.. | wikipedia | yo |
Ìyá rẹ̀, Ènìyàn Funfun, ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà, Stanley Ann Dunham, jẹ́ ọmọ ilé ẹ̀kọ́ Unifasiti láti ìlú Wichitta, ìpínlẹ̀ Kansas.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí ìyá rẹ̀ lòdì sí àjọṣe àwọn méjẽjì, ṣùgbọ́n wọ́n fẹ́ ara wọn ní ọdún 1960.Ọdún méjì lẹ́hìn tí wọ́n bí Obama, baba rẹ̀ ló sì Howard fún ìtẹ̀síwájú ẹ̀kọ́ rẹ̀, ṣùgbọ́n kò mú ẹ̀bi rẹ̀ lọ nítorí àìsí owó.. | wikipedia | yo |
Ní ìgbà ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni Howard, Obama- àgbà fẹ́ Ruth nídèand, ẹni tí ó bá padà sí orílẹ̀ èdè Kenya lẹ́hìn ìparí ẹ̀kọ́ rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ruth nídèand jẹ iyawo rẹ̀ ẹkẹta, wọ́n sì ní ọmọ meji.. | wikipedia | yo |
Ní orílẹ̀ èdè Kenya, Obama- àgbà bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ilé iṣẹ́ tí ó nwá epo rọ̀bì, lẹ́hìn èyí, ó ṣiṣẹ́ fún ìjọba, gẹ́gẹ́bí olóòtú ètò ọrọ̀ ajé.. | wikipedia | yo |
Ó fi ojú kan ọmọ rẹ̀, Obama, ní ìgbàkan péré- ní ìgbà tí òní tọ̀hún pé ọmọ ọdún mẹ́wàá.. | wikipedia | yo |
Obama- àgbà fi arapá nínú àgbákò òkò nípa èyí tí ó sọ ẹ̀ṣẹ̀ méjẽjì nù.. | wikipedia | yo |
Ní ìgbà tí ó pe ọmọ ọdún mẹ́rìn-dì-làádọ́ta, ní ọdún 1982, ó sọ ẹ̀mí rẹ̀ nù nínú àgbákò ọkọ.Lẹ̀hìn ìyapa pẹ̀lú bàbá Obama, ìyá rẹ̀ fẹ́ lóló soẹ̀tọ́, ọmọ ilé ẹ̀kọ́ gíga Unifasiti láti orílẹ̀ èdè Indonesia.. | wikipedia | yo |
Barack Obama ní ọbàkan, obinrin, ọmọ lòlò àti Stanley Ann.. | wikipedia | yo |
Stanley Ann Dunham pẹ̀hìndà ní ọdún 1995.Ìwé tó kọ Obama, Barack.. | wikipedia | yo |
RePrint Edition, 2004; ISBNISBN-4000-8_ Susan Obama, Barack.. | wikipedia | yo |
ISBN0-307-23769-9.Àwọn ibùdó lórí Interflows Obama ‘08 — Barackóbá.com ibi-iṣẹ́ Obama ni ilẹ̀ àwọn alàgbà aṣòfin ilẹ̀ Amẹ́ríkà</àníyàn> ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1961àwọn Ààrẹ ilẹ̀ AméAméka ẹlẹ́bùn Nobel fún Àlámíràn Ọmọ Áfríkà Ga Gavel Nobel ara Améma Aramíràn Aṣòfin Aṣòfin.S..S..S.. | wikipedia | yo |
Ọmọ Afrika Ameria oloselu ara Amerika alagba from aṣofin orilẹ-ede Amẹrika lati Illinois.. | wikipedia | yo |
Oloye Sunday Adeniyi Adeye (ojoobi- ojo kejilelogun osu SS, odun 1946), ti a mo si King Sunny Ade, je olorin Jùjú ọmọ Naijiria, ònkọ̀tàn-orin ati Onimọ-ọlọ́pọ̀ irinṣẹ́.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olórin Takasúfèé tí ó ṣe àṣeyọrí káríayé, tí wọ́n sì tún mọ̀ ọ́ bí ọ̀kan lára àwọn olórin tó lámìlà nígbà gbogbo.. | wikipedia | yo |
Sunny Ade da ẹgbẹ́ olórin àkọ́kọ́ rẹ̀ sílẹ̀ ní ọdún 1967, ti ó pè ní African Beats.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí ó di onílùúmọ̀ọ́nkà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó dá ẹgbẹ́ akọrin rẹ̀ sílẹ̀ ní àkókò 1970, Sunny Adé bá Ile-iṣẹ Island Records ṣiṣẹ́ ní 1982 ti àwọn àwo rẹ̀ Jùjú Music (1982) àti SyChté System (1983) sì jẹ́ àgbà wọlé ní káríayé.. | wikipedia | yo |
SyChté System yìí ló mú wọlé gẹ́gẹ́ bíi ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n du ipò Grammy, tí ó mú jẹ́ olórin àkọ́kọ́ láti Nàìjíríà tí yóò dé irú ipò bẹ́ẹ̀.. | wikipedia | yo |
Iṣẹ́ Awo rẹ̀ tí ó pè ní odù náà jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà fún Grammy.. | wikipedia | yo |
Sunny Ade ni ó jẹ́ alága ẹgbẹ́ olórin ti Nàìjíríà ni àkókò yìí.Adégún ni a bí ni Òṣogbo sí ìdílé ọba ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti Òǹdó.. | wikipedia | yo |
Nitori naa ṣe ni Ọba Oloye Ọmọọba ti awọn ara ilu Yoruba.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ jẹ́ Organist ilé ìjọ́sìn, ti ìyá rẹ̀ jẹ́ oníṣòwò kan.Adé fi ilé-ìwé Grammar sílẹ̀ ni Òndó lábẹ́ ète ti lílọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Èkó.. | wikipedia | yo |
O gba bi ọkan ninu awọn akọrin Pop olorin akọkọ ti Afirika lati ni aṣeyọri Kariaye, a ti pe ni ọkan ninu awọn akọrin ti o ni agbara julọ ti gbogbo akọkọ.. | wikipedia | yo |
Ń Oṣù Kẹta ọdún 2017, ó ti yan àjẹkù fún ipolongo bíbẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Me.. | wikipedia | yo |
Minisita fun alaye ti orile-ede Naijiria lai Mohammed .King Sunny ni ipa nipasẹ Aṣaaju-ọna Jùjú Tunde Nightingale ati awọn eroja ti o ni agbara alailẹgbẹ lati 'so wa mbẹ' ara ti Jùjú.O da ipilẹ King Sunny Ade Foundation, agbari ti o ba pẹlu ile-iṣẹ iṣe adase kan, ipinlẹ ti Ile-iṣẹ gbigbasilẹ aworan, ati Ile fun Awọn akọrin ọdọ.O jẹ olukọni ni abẹwo ni Ile-ẹkọ giga Obafemi Awolowo, Ile-Ife ati Olugba ti Aṣẹ ti Federal Republic.Ere Ori Itageni Awọn ọdun 1970 ati ọdun 1980 Ade bẹrẹ irin-ajo Irin-ajo ti Ilu Amẹrika ati Yuroopu.. | wikipedia | yo |
Iṣẹ ipele rẹ ni a ṣe afihan nipasẹ awọn igbese ijó oníjàgídíjàgan ati agbara G.itusilẹ agbaye ti Jùjú orin ati Irin-ajo ti o tẹle ni "O fẹrẹ ṣọkan lápapò nipasẹ awọn olotótó (ti ko ba jẹ awọn alabara) nibi gbogbo"A ṣapejuwe Ade ni The New York Times bi "Ọkan ninu awọn oludari ẹgbẹ nla agbaye”, ninu igbasilẹ bi "Ẹmi ti Àfonífojì Titun, Ariwo rere ti a yoo nilati fun akoko diẹ lati wa" ni ni Sokoto ti Awọn ohun ohun ==== Omo ilu Yoruba, Orin Sunny Adega ni Ìjúwe laarin awọn, laarin awọn ohun-elo miiran, Ilu ti sọrọ -ede ohun abinibi-ede abinibi si awọn gbongbo Yoruba rẹ, gìta ati ohun elo elo Yoruba julọ si orin.. | wikipedia | yo |
Sunny Ade pelu egbe re se ero ara oto reitọkasi == awon omo YORÙ olorin ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Robert "Bob Nesta Marley (6 February, 1945 – 11 May, 1981) jẹ́ olórin reggae ọmọ ilẹ̀ Jàmáíkà.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1945àwọn Ojoaláìsí ní 1981Àwọn olórin ará Jàmáíkà.. | wikipedia | yo |
reggae jẹ́ ẹ̀ka orin tí ó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ láti ilẹ̀ Jàmáíkà.Orin.. | wikipedia | yo |
UNICEF ní èdè Gẹ̀ẹ́sì dúró fún United Nations Children's Fund (Àjọ Ìṣọ̀kan Àwọn Orílẹ̀-Èdè Fún Àwọn Ọmọdé).Ìtọ́kasí Àwọn àgbájọ àwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn káríayé.. | wikipedia | yo |
Ìwọ̀n ẹyọ sí sí ti à mọ́ bí bí ìwọ̀n sí ní (láti Èdè Fránsì tó jẹ́ lé agbo International D'12] jẹ́ ọ̀nà ìwọ̀n (Ki bẹ́ẹ̀dì.2] Cell Cell Nigga Gbodo OyO Gami KLOLO OLO OLO </ble 2 E E | </ble N 2 Rece O 2 E 2 Resórí O | Mo O Kan OyO E K Rece 2 Hice | </ble 2 =PA8] N Tuntun N N Kan Tuntun O | Tuntun O N W Tuntun Re Re Rece O M 2 ↑ Tom Re Re Baby N Lo D (www www | O </ble N Ch N 2 N 2 N 2 N 2 N M 2 2 N 2 - Wori - N < / 2 </ble 2 N 2 D 2 / W.2 W </ble 2 N 2 ↑ Stop _*2 N 2 N 2 N 2 N N Tuntun 2 N 2 N Tuntun Lo Tuntun 2 N 2 N 2 N Tuntun N Tuntun N N 2 N 2016 N Stop Pi O M 2 2 ↑ Eaila Tom Mai ( X ( 2 N N 2 / EyO E =PA8] N 2 = " 10 = E Tom =PA8 _ _*N 2017 : OyO 2 ↑ 1994. | wikipedia | yo |
Anc ní èdè Gẹ̀ẹ́sì dúró fún African National Congress (yun ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ torílẹ̀-èdè Áfríkà).. | wikipedia | yo |
Anc jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú ní ilẹ̀ Gúúsù Áfríkà.Ìtọ́kasí Gúúsù Áfríkà.. | wikipedia | yo |
Ekẹhin jẹ oluilu ati ilu t'otobi ni orilẹ-ede ZAMBIA.Ìtọ́kasí Zambiawọn oluilu ni Afrika.. | wikipedia | yo |
aristoTulu ránka onímọ Araayéijọ́un ọmọ ile Greesi, akeko Plato àti Olùko aleale eni Ńlá.Ìtọ́kasí àwọn Amòye.. | wikipedia | yo |
Àwọn orílẹ̀ tó wà lagbaye ní Asia, Africa, North America, South America, Antarctica, Europe, àti Australia.Agbegbe àti pípọ̀ àkójọ ilé àwọn orílẹ̀ ní 148,647,000 km, tàbí 29.1% ilé ayé (5,0,0,600 km). | wikipedia | yo |
ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ jẹ́ ìrẹ́pọ̀ bí ẹlọ́pọ̀ àwọn èrò kódò káàkiri àgbáyé fún ipasí ìyà àti ìmọ̀.. | wikipedia | yo |
Ni ede geesi o wa lati oruko Inter - Network, nitori naa ni ede Yoruba a n pe ni Íńtánẹ́ẹ̀tì.itọkasi.. | wikipedia | yo |
Anhánbu tabi Salóníkà je ilu ni orile-ede Griji awon ilu ati Abule ni Griisi.. | wikipedia | yo |
RaÌlá Amolo odinga (born January 7, 1945) jẹ oloselu ọmọ ile Kenya, lọwọlọwọ o jẹ alakoso agba ile Kenya ninu ijoba ìdarapọ̀.A bi I ni Maseno, Kizumu District, Vza Prorince ni January 1945.. | wikipedia | yo |
Ó rí ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ ní 1965 èyí tí ó fi lọ kàwé ní Technical University of Magdeburg (tí ó jẹ́ ará Otto von Guẹ̀riche University of Magdeburg) ní East Germany.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1970, ó jáde ó sì gba oyè lórí ìtẹ́wọ́gbà níýìláti.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó dé Kẹ́nyà, ó ṣe olùkọ́ ní University of Nairobi kí ó tó lọ máa ṣe òsèlú.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1975, wọ́n sọ ọ́ di Deputy director of the Kenya Buréan of standards ise ti o se titi ti won fi so o si ìhámọ́ ní 1982.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fi í sílẹ̀ ní oṣù kẹfà 1988, wọ́n tún tún un mú ní oṣù kẹjọ.. | wikipedia | yo |
Wọ́n fi sílẹ̀ ní ọjọ́ kejila oṣù kẹfa 1989 wọ́n tún mú un pada ní ọjọ́ karun-un oṣù keje ọdún 1990 pẹlu Keneth mátìba ati Charles Rúbia.. | wikipedia | yo |
Bí wo ṣe dá a sílẹ̀ ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹfà ọdún 1991, ńṣe ni ó sá gba Norway lọ ó ní wọ́n fẹ́ pa òun.. | wikipedia | yo |
O pada sí Kenya ní 1992, o dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Ford èyí tí bàbá rẹ, jaramọn Bonïga Odìnga ń darí.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí bàbá rẹ̀ kú ní Oṣù ìgénì ọdún 1994 tí Michal wáí́wa Kakoko di olórí ẹgbẹ́ náà ra ì ta ó ṣùgbọ́n ó fidi rẹmi èyí ló mú un ( un (be) kúrò nínú ẹgbẹ́ náà tí ó sì dara pọ̀ mọ́ National Development Party (FIFIkasí àwọn ará Kenya.. Àwọn ara Kenya.. Àwọn ara Kenya * lọ ti oṣù Kenya * ti ọdún [ìparun ọdún [ tí ó yẹ ọdún * * * * * * * * * * * * ti o sí ọdún náà ti * * * * * ti o si National ( National Party ( National náà * ní ọdún rẹ̀ sí un ti ọdún rẹ̀ ti di eni * * ti ọdún rẹ̀ tí ó gbé sí ara yìí tí ó mú ní ọdún rẹ̀ ( 13 tí ó ti o sí ọdún náà * * * **** * * tí ó sì dara * ***** * * * ** | wikipedia | yo |
A bí kíèèrà ní ọjọ́kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù Kọkànlá ọdún (1931–2022) orúkọ ìbatisí rẹ̀ ní Emilio Stanley ṣùgbọ́n kò pé tí ó fi orúkọ yìí sílẹ̀ tí ó ń jẹ́ orúkọ Kiku.. | wikipedia | yo |
History àti Political Science ni ó kà ní Makerere University ní Kampala, Uganda.. | wikipedia | yo |
Òun ni ó ṣ eipo kìíní ninu kíláàsì rẹ̀ nígbà tí ó jáde ní 1955.. | wikipedia | yo |
O fi Eko-ọfẹ lo London School of Economics nibi ti o ti ka Public Finance ti o si gboye B.Sc ni 1959.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe iṣẹ́ olùkọ́ díẹ̀ kí ó tó fi iṣẹ́ náà sílẹ̀ lọ máa ṣe òṣèlú.. | wikipedia | yo |
Wọ́n jọ dá ẹgbẹ́ Kenya African National Union (kánú) sílẹ̀ ní ní 1960 lẹ́yìn ọdún méjì tí ó ti wà nílẹ̀ aṣofin,wọ́n sọ ọ́ di minister of Commerce and Industry.. | wikipedia | yo |
Nigba ti arap Moi di are leyin iku jọmọ Kenyatta ni 1978, o di igba keji are.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1990, o da ẹgbẹ tirẹ ti o n jẹ Democratic Party silẹ ni ọdun 2002, o di Aare Kenya.itọkasi awọn ara Kenya.. | wikipedia | yo |
Eleaza Dagunweku Festivalòkúa bi i ni 18th January, 1932 ni Ipinle Anambra ni ile Naijiria.. | wikipedia | yo |
O lọ si Ile-ẹkọ ni Merchant of Light School, Ọba; University of Ibadan, Institute of Public Administration, London; Catgu Institute, France.. | wikipedia | yo |
O jẹ secretary Commonwealth.itọkasiàwọn ara Nàìjíríààwọn akọwe-àgbà àjọní awọn orilẹ-ede.. | wikipedia | yo |
Felix Omoiọṣẹ́je aizọbẹ̀ ohiweiweRe je onisowo omo ile Naijiria.. | wikipedia | yo |
A bí i ní 18th January, 1937 ni Owan ní Ìpínlẹ̀ Edo ní ilé Griaté.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ní St David's School Arbiosi ní 1944-1946; government school, Owerri 1947-1950, government Secondary school, Owerri 1951-1955; Nigerian College of arts, Science and Technology 1956-1958; University College (tí ó ti di University of Ibadan) Ìbàdàn 1958-1961; ó dara pọ̀ mọ́ Nigerian Breweries ní 1962 gẹ́gẹ́ bí i manager tí ó wà lẹ́nu ìkọ̀sẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ó sì bẹ̀rẹ̀ síí ní ìgaga títí tí ó fi di chairman àti Chief Executive Officer ilé-iṣẹ́ náà ní 1997.. | wikipedia | yo |
Ó di ṣe a làjà léver brothers PLC (tí ó dì di uníléver), ó ṣe alága Virgin anline .. | wikipedia | yo |
O jẹ Fellow Nigerian Marketing Association (NMA), Gographical Fcuty of Nigeria, Institute of Directors àti Adverlising Praciers of Nigeria.Àwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Herbert Samuel Heelas Macaulay (November 14, 1864—May 7, 1946) je oloselu ọmọ orile-ede Naijiria.Ọmọ-ọmọ bisooobu Samuel Ajayi Crowther ni Herbert Macaulay jẹ.. | wikipedia | yo |
Ó kú ní ọdún 1946 níbi tí ó ti n ṣe ìpolongo ìbò.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1864àwọn Ojoaláìsí ní 1946àwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Benjamin Nnamdi Azikiwe (November 16, 1904 – May 11, 1996) tabi Zst je omo orile-ede Naijiria-ede Naijiria, lati ẹya Igbo.. | wikipedia | yo |
Ọ̀kan nínú àwọn olóṣèlú pàtàkì ni Azikiwe jẹ́ ni Nàìjíríà, ó sì jẹ́ aṣíwájú fún Ifẹ̀gbega orílẹ̀-èdè ara ẹni ní Nàìjíríà lódeòní, bẹ́ síni ó tún jẹ́ Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà àkọ́kọ́ ní ìgbà òṣèlú àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà lẹ́yìn ìgbàtí Nàìjíríà gba òmìnira ní ọdún 1960.Igba Ewea bí Azikiwe ní ọjọ́ 16 Oṣù Kọkànlá ọdún 1904 ni Zùnyàráun, ní apá àríwá Nàìjíríà Ètòb Àjọgun Àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ Igbo lati apá ìlàoòrùn.. Naijiria.. | wikipedia | yo |
Nnamdi tumọsi "Bàbá mi wa laaye." leyin eko re Methodist High School ni Eko o gbéra lọ si ilẹ̀ Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Níbẹ̀ o ka wẹ̀ ní Yunifásítì Howard ní Washington, D.C.. | wikipedia | yo |
Kó tó di pé ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Yunifásítì Lincoln ní ìpínlẹ̀ Mídáraté ní 1930.. | wikipedia | yo |
O di eniyan dudu akọkọ ti yoo jẹ gomina-gbogbogbo fun Nigeria ni 1960.. | wikipedia | yo |
Nnamdi wa ri kini yi bi buburu, nipa ere agbabọọlu ati oselu.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1934, wọn o jẹ ki Zst kopa ni eresísá nitori pe wọn ko fẹ ki Naijiria kopa ni ere na.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí òṣì ṣẹlẹ̀ pé wọ́n jẹ́ kí Zst kópa nítorí pe ó jẹ́ ọmọ ibo, Nnamdi wá dá gbe tiẹ̀ sílẹ̀ tí ó jẹ́ (Z's athleti Club ZZ) ẹgbẹ́ yi fun gbọ́ àwọm on Nàìjíríà tí ó ní ìfẹ́ oríṣiríṣi eré ìdárayá tó wà.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1942 ẹgbẹ yi ṣe akọkọ ni ire idaraya ti Ilu Eko at ere iranti ogun.. | wikipedia | yo |
Leyin ti won pari ere yi ni odun ye., wa si eka egbe yi kakiri Nigeria.itọkasiàwọn ara Naijiriaàwọn ile Naijiria.. | wikipedia | yo |
Al-Hji Sir Ahmadu Ibrahim Bello (June 12, 1910 – January 15, 1966) ti ọpọlọpọ mọ si sir Ahmadu Bello je eni ti o wa nidi dida ariwa Nigeria kale nipasẹ ominira Naijiria ni odun 1960.. | wikipedia | yo |
Oun si ni adari(Premier) akọkọ ati ẹnìkan soso ti o di Premier Ariwa Naijiria, ipo ti o di ipo naa mu titi ti wọn fi sekupa ni ọdun 1966.Oun tun ni adari Northern People's Congress, ẹgbẹ oselu ti o wa ni ijoba nigba naa, awon Ọ̀tọ̀kùlú Hausa-Fúlàní si ni won po ni ẹgbẹ oselu naa.. | wikipedia | yo |
Wọ́n kọ́kọ́ yàn láti jẹ́ aṣòfin ní agbègbè ibi tí ó wà kick tó padà di Mínísítà ìjọba.. | wikipedia | yo |
O gbiyanju lati si Sultan Ipinle Sokoto kick to wọ inu oṣelu.itọkasiàwọn Ọjọ́ìbí ni 1910àwọn Ojoaláìsí ní 1966àwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Yunifásítì jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga àti iṣẹ́Wadi tí ó fún ni ní ìwé-ẹ̀rí fún ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ni bí èyí-kẹyí ẹ̀kọ́ tó bá wùwá láti ní ìmọ̀ àrídájú níparẹ̀... | wikipedia | yo |
Ìkàrẹ̀-Àkókó tàbí Ìkàmọ ni ṣókí jẹ́ olú ìlú agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ àríwá-ìlà ọ̀run àkọ́kọ́ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ olú-ìlú tẹ́lẹ̀-tẹ́lẹ̀ fún gbogbo agbègbè àkọ́kọ́ lápapọ̀ ní ìpínlẹ̀ Òndó.. | wikipedia | yo |
Àwọn ìlú tí ó wà ní agbègbè Ìkàrẹ̀ tẹ́lẹ̀ ní ọkà-àkọ́kọ́ ,Ísúa àkọ́kọ́ , ọgbàgi-Àkókó, Òkèàgbè-Àkókó, irun-àkọ́kọ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Ìkà-Àkókó ni olú ilé iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ àkọ́kọ́ North-East Local Government wà.. | wikipedia | yo |
ilú naa si tó iye ọgọrun un kìlómítà (100 km) si ilú Àkúrẹ́ ti ó jẹ́ olú ilú fún gbogbo ìpínlẹ̀ Ondo lápapọ̀.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni àwọn ọmọ Ìkà kò fi ìwé kíkà ṣeré, tí ó sì ti gbé wọn dé ibi àti ipò gíga ní gbogbo àgbáyé.Eto Oro-Ajé Ìkà jẹ́ Ojúkò Ọjà fún Ọ̀pọ̀ àwọn ìlú tí wọ́n wà ní agbègbè rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọjà tí wọ́n wà ní ìlú Ìkà bí Ọjà Ọba tí ó wà ní àdojúkọ ilé ìfowó-pamọ́ First Bank tẹ́lẹ̀, Ọjà Okorẹ́ , Ọjà Òṣẹ̀lẹ̀ ni ó jẹ́ Ọjà tí wọ́n ti ń sábà ma ń ta àwọn nkan Ìṣèṣè ìbílẹ̀ jùlọ ní Ìkà, Ọjà jùyì , àti àwọn Ọjà míràn tí wọ́n so Ìkà pọ̀ mọ́ àwọn ìlú míràn tí wọ́n wà ní agbègbè rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni wọ́n jẹ́ ẹlẹ́sìn ìmàle, Kìrìstẹ́nì.Ìṣesí ìlú Ìkà Ìṣesí ìlú náà bá ti àwọn ará ilẹ̀ Pọ́túgà àti ti àwọn Lárúbáwá mu nínú ẹ̀sìn, ìṣesí tí àwọn Potogí ni ó wọ ìlú náà ní àárín ọ̀rúndún kẹrìndínlógún (16th century) nígbà tí òwò ẹrú bẹ̀rẹ̀ ní agbègbè náà.. | wikipedia | yo |