cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Tse ni o dabi ẹni to ṣówó ti ko jẹ̀rẹ̀.Sugbon ti Oloye Ogunde se ti awon bii Ola Balogun, Adeyemi Afolayan ti gbogbo eniyan mo si "Ade Love" ati Moses Oluya ti won n pe ni "Baba Salate..
wikipedia
yo
GẸ́GẸ́ BÍ AUTTY ÒWEns-E (2004) ṢE SỌ, gbogbo fíìmù tí wọ́n ṣe pẹ̀lú owó tí wọ́n yá ní ilé-ìfowópamọ́, wọ́n jẹ́ gbèsè tí púpọ̀ wọn ó tilẹ̀ dábàá àti ṣe fíìmù àgbéléwò mọ́ lẹ́yìn náà..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bi ohun ti “Ade Love” sọ kí ó tó kú ní ọdún 1995 nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan tí wọ́n ṣe fún; ó ṣàlàyé bí òun ṣe yá owó ní Báńkì láti ṣe fíìmù rẹ̀ "Destiny" (Àyànmọ́)..
wikipedia
yo
Ó ní ní ìgbà náà, dọ́là kan jẹ́ déédé naira mẹ́wàá, ṣùgbọ́n ní ọjọ́ yìí, ó di naira kan-dínlógún fún dọ́là kan..
wikipedia
yo
Ó ní òun ní láti yá owó sí ni láti san owó tí òun yá ṣe fíìmù náà..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, àwọn bíi ọlá balógun àti Herbert Ògùndé bẹ̀rẹ̀ sí níí ṣe fíìmù pẹ̀lú irinṣẹ́ tuntun..
wikipedia
yo
Eyi jẹ ki àwọn fiimu wọnyi di gbajumọ ni ilẹ̀ Naijiria ati ni okeere..
wikipedia
yo
Ogunde ṣe "Jaiyesinmi", "aropin n'tẹnia" àti àyànmọ́..
wikipedia
yo
Láàárín ọdún 1993 sí ọdún 1996, àwọn tí wọ́n ń ṣe fíìmù Yorùbá ti pọ̀ sí..
wikipedia
yo
Fíìmù Yorùbá tí ó jáde ní àkókò yìí lé ní igba (200)..
wikipedia
yo
Oyin Adéjọbí náà ṣe fíìmù kan tí ó pè ní "Orogún Adédigba" ní ọdún 1995..
wikipedia
yo
Yàtọ̀ sí èyí, Yemi Guunbi ṣe fíìmù kan tí ó pè ní "Ẹ̀bùn Olúwa" ní ọdún yìí kan náà..
wikipedia
yo
Àwọn òṣèré bíi Jide Kosoko àti Sola fóṣù ṣe fíìmù kan tí wọ́n pè ní "ọkọ ìyàwó”.Lẹ́yìn tí àwọn òṣèré yìí ṣe fíìmù yìí tán, àwọn òṣèré mìíràn bẹ̀rẹ̀ sí í gbé fíìmù tiwọn náà jáde jáde..
wikipedia
yo
Bí wọ́n bá ní kí wọ́n ka oríṣi fíìmù Yorùbá tí ó ti jáde, yóò tó ìdá mẹ́fà Fíímù tí ó ti jáde ní ilé-iṣẹ́ àwọn onífíìmù tí ó gbajúmọ̀ nísìnyí..
wikipedia
yo
Orúkọ tí wọ́n ń pe ilé-iṣẹ́ náà, tí ó kó àwọn òṣèré mọ́ àwọn tí n ṣe fíìmù jọ ni wọ́n n pè ní Nollywood..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ fiimu Yoruba ti tobi si; akoonu fiimu wọn si ti n yipada si ti atijọ ti o jẹ wi pe ọrọ ẹsin ibile, Efe ati bẹẹ bẹẹ lọ, ni o n jẹ ẹ logun.Ipa àwọn fiimu Yoruba láwùjọ Yorubaohun pataki kan ti o ya fiimu Yoruba sọtọ ni ede amú..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí a ṣe mọ̀ pé àwọn Yorùbá kìí ń sọ̀rọ̀ lásán, wọ́n máa ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lú làákàyè àti ọgbọ́n..
wikipedia
yo
Àwa náà sì mọ̀ pé èdè Yorùbá yìí kún, ó dùn, ó ṣe pàtàkì, ó sì jọjú gidigidi..
wikipedia
yo
Tí wọ́n bá kọ eré, ìṣẹ̀lẹ̀ lájùlọ àti ọgbọ̀n inú rẹ̀ ni wọn ó kó jọ..
wikipedia
yo
àkóónú eré wọn a máa lọ láti orí ìbálòpọ̀ tí ó lẹ́tọ̀ọ́, ìwà ìbàjẹ́ láwùjọ láàárín ọ̀tọ̀kùlú àti ìjọba, ìjà ìyálé àti ìyàwó, ìrírí ayé, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Èdè Yorùbá tí wọ́n fi ń gbé ìtàn wọn kalẹ̀ yìí jẹ́ kí ó yé gbogbo mùtúmùwà ohun gbogbo tí wọn ń ṣọ́..
wikipedia
yo
Ó sì jẹ́ kí tàgbà tọmọdé, akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́, kòfẹ̀sọ̀ àti àgbẹ̀ rí ẹ̀kọ́ kan tàbí òmíràn dìmú nínú fíìmù wọn..
wikipedia
yo
Wọ́n kì í dédé sọ̀rọ̀ bí kò bá ṣe wí pé ó lóhun tí ònkọ̀tàn rí..
wikipedia
yo
Àwọn òṣèré náà sì máa ń gbìyànjú láti túmọ̀ gbogbo ohun tí ó bá yẹ kí wọ́n sọ kí ó lè yé gbogbo ènìyàn.Ohun mìíràn tí a tún gbọ́dọ̀ ṣàkíyèsí ni pé àwọn olóṣèlú a máa fi àwọn eré ìgbàlódé orí ìtàgé àti ti inú fiimu polongo ara wọn nígbà ìdìbò..
wikipedia
yo
A rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àpẹẹrẹ, nínú àwọn fíìmù àgbéléwò tí ó ti wà lóri àtẹ..
wikipedia
yo
Ọ̀kan nínú àwọn tí wọ́n lọ láti kìlọ̀ nípa ìdìbò, ṣe ìlérí àwọn ará ìlú àti tí wọ́n fi pe àfiyèsí àwọn ará ìlú nígbà ìdìbò ní fíìmù tí wọ́n pè ní "Olu-Ọmọ-Il..
wikipedia
yo
Ẹni ti ó bá ṣe àfiyèsí ti ó kún ninu fiimu yìí yóo mọ̀ wi pé ọ̀kan ninu àwọn olùdíje fún ipò Gómìnà ni ìpínlẹ̀ Èkó ni ó fi polongo..
wikipedia
yo
A lè sọ wí pé fíìmú máa ń jẹ kí oye àwọn ènìyàn kún sii..
wikipedia
yo
A tún gbọ́dọ̀ ṣàkíyèsí pé kìí ṣe gbogbo fíìmù ni ó ń ko ipa gidi ní àwùjọ, àwọn kan tile maa ń polongo ìwà ìje ìje.iwe ti a ̀àgbéyẹ̀wò ìfara ẹ̀ka-èdè nínú fíìmù gbé-ede Olodumare-O- bu-òwa, ati agogo-ẹ̀wo kan nínú asekagba Ibb.A (hons Yoruba Obafemi OWA-ìsin Awóko Ọwọ́lè Olùwàwọ́lé Adelẹ̀ Okini O lẹ́ 2007.. Dr.. ) Dr - Dr.. ) ↑ ọdún York.. Àwọn kan ni ó da ni * ole ni FIwo FIwo mú ni kìí ni adugbo agbá ni ó n ko * ni oore- gbogbo kan ni ó n da iye ipa mọ́ ní gbogbo tí ó n da dara- ] nínú agbo yìí– ] Nta ni ó da ọdún kan ni ó n bu yẹ ní Ọ̀dara-ede kan nínú owó pé ni ọdún Film Adewe - Dr- ] N tún yẹ - wọ́lẹ̀ ni kìí ṣe gbogbo ọdún York ni ó n bu ni àwọn èṣẹ we lati tipa ni adugbo rẹ̀ pé ọmọ ni ó tún gbé ọdún rẹ̀ - FI kan ni ó n polongo ní agogo ní alaafia. Àwọn kan ni ti o ga ni o tun ni agbo pé ò ọdún rẹ̀ nínú agbo ní o ń ko ipa rẹ̀ ni àwùjọ rẹ̀ ni ti o yẹ ẹ̀ro ni * ni a gbì ẹ̀ka ẹ̀ka- nínú ọdún rẹ̀- ] Ní oyin- ati elé kan nínú asekagba I yẹ (i-ẹ̀ràlẹ̀. Yorùbá. Ní ọdún olè*_
wikipedia
yo
Frederick Douglass (orúkọ àbísọ Frederick Augustus Washington Bailey, February 1818 – February 20, 1895) jẹ́ ará Amẹ́ríkà alátúnṣe, alásọdùn, Olùkọ̀wé àti bàbáalu..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tó sákúrò ní oko-ẹrú, ó di olórí ẹgbẹ́ ìrìnkankan Apokoérúrẹ̀, pẹ̀lú ọ̀rọ̀ kankan rẹ̀ àti ìwé alòdì sí oko-ẹrú tó kọ..
wikipedia
yo
Ohun ló dúró bí àpẹrẹ tólòdì sí ìjiyàn àwọn akónilẹ́rú pé àwọn ẹrú kò ní làákàyè láti ṣiṣẹ́ bí ọmọ Amẹrika alómìnira..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn ará àríwá nã sì tún nira láti gbàgbọ́ pé irú ẹni unla bayi ti jẹ́ ẹrù tẹ́lẹ̀.Douglass kó ọ̀pọ̀ ìwé ìgbésíayéaraẹni, nibi tó ti ohun tọdún júwe ìríré nínú oko-ẹrú nínú ìwé ìgbésíayéaraẹni tó kọ ní 1845, ìtàn ìgbésíayé Frederick Douglass, ẹrù ará Amẹ́ríkà, tó kópa kíkan nípa fífọwọ́kun ipòkóẹrúa..
wikipedia
yo
Ó tún kọ́ ìwé Ìgbésíaraẹni méjì míràn, èyí tó gbẹ̀yìn tọkọ únjẹ, ìgbbesi àti ìgbà Frederick Douglass, tójẹ́ títẹ̀jáde ní 1881 tó sì dálórí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó wáyé nígbà àti lẹ́yìn ogun abẹ́lé..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ogun abẹ́lé, Douglass kò kọsẹ̀ nínú ìjàgudu orílẹ̀-èdè Amẹrika lati di “Ilẹ̀ Olómìnira” Lóòtọ́..
wikipedia
yo
Láì lọ́wọ́ únwá ó di ọmọ Áfríkà Amẹrika àkọ́kọ́ tó jẹ́ dídálórúkọ fún ipò igbákejì ìya Amẹ́ríkà bí ẹlẹ́gbẹ́ àjọ ìdu sí Victoria Woodll ti ẹgbẹ́ òsèlú kékeré Rights Rights Party..
wikipedia
yo
Douglass di opo ipo ijoba mu.Douglass nígbàgbọ́ gidigidi ninu Ijedọ́gba gbogbo ènìyàn, bóyá ó jẹ́ Adúláwọ̀, àbò, abínibí ara Amẹ́ríkà, tàbí àṣeàṣejìlù, ó gbajúmò pé ó sọ pé, "Un ò parapọ̀ mọ́ ẹni yíòwù láti ṣe rere, unkò ní parapọ̀ ṣebàjẹ́ pẹ̀lú ẹnìkankan.”Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1818àwọn ọjọ́aláìsí ní 1895àwọn Ọmọ Áfríkà Américo Oabeko Arare Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì tàbí Ingd jẹ́ orílẹ̀-èdè ará ìṣọ̀kan Ilẹ̀-ọba.Àwọn àgbègbè Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sìlist of Regions East Midlands East of England Greater London North East England North West England South East England South West England West Midlands Yorkshire and the humbẹ́rítọ́kasí Britani..
wikipedia
yo
Ibrahim Badamasi Babangida (Ọjọ́ìbí August 17, 1941) jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ọ̀gá Ológun tó ti fẹ̀yìntì..
wikipedia
yo
Ọ̀gágun Babangida fi ìgbà kan jẹ́ olòrí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ọdún 1985 títí dé 1993.Ìtọ́kasí àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríààwọnàwọn ọ̀gágun ará Nàìjíríààwọn ògá Ọmọsẹ́ Agbógun Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọdún kan jẹ́ iye àsìkò tí ó gba Pitlan ilẹ̀-ayé láti fi yípo oòrùn ká lẹ́ẹ̀kan péré..
wikipedia
yo
Ní fífágún, a leè fi èyí múlẹ̀ fún pílanetí yó wú..
wikipedia
yo
Ìkéde káríayé fún ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn àkọ́so bí ó ti jẹ́ pé ṣíṣe àkíyèsí iyì tó jẹ́ àbímó̩ fún Ẹ̀dá àti ìdó̩gba ètò tí kò s̩eé mú kúrò ti è̩dá kò̩ò̩kan ni, ni òkúta ìpìlè̩ fún òmìnira, ìdájó̩ òdodo àti àlàáfíà lágbàáyé.Bí ó ti jé̩ pé àìka àwo̩n è̩tó̩ o̩mo̩nìyàn sí àti ìké̩gàn àwo̩n è̩tó̩ wò̩nyí ti s̩e okùnfà fún àwo̩n ìwà búburú kan, tó mú è̩rí‐o̩kàn è̩dá gbo̩gbé̩, tó sì jé̩ pé ìbè̩rè̩ ìgbé ayé titun, nínú èyí tí àwo̩n ènìyàn yóò ti ní òmìnira òrò̩ síso̩ àti òmìnira láti gba ohun tó bá wù wó̩n gbó̩, òmìnira ló̩wó̩ è̩rù àti òmìnira ló̩wó̩ àìní, ni a ti kà sí àníyàn tó ga jù lo̩ ló̩kàn àwo̩n o̩mo̩‐Ènìyàn,bí ó ti jé̩ pé ó s̩e pàtàkì kí a dáàbò bo àwo̩n è̩tó o̩mo̩nìyàn lábé̩ òfin, bí a kò bá fé̩ ti àwo̩n ènìyàn láti kọjú ìjà sí ìjo̩ba ipá àti ti amúnisìn, nígbà tí kò bá sí ò̩nà àbáyo̩ mìíràn fún wo̩n láti bèèrè è̩tó̩ wo̩n,bí ó ti jé̩ pé ó s̩e pàtàkì kí ìdàgbàsókè ìbás̩epò̩ ti ò̩ré̩‐sí‐ò̩ré̩ wà láàrin àwo̩n orílè̩‐èdè,bí ó ti jé̩ pé gbogbo o̩mo̩ Àjo̩‐ìsò̩kan orílè̩‐èdè àgbáyé tún ti te̩nu mó̩ ìpinnu tí wó̩n ti s̩e té̩lè̩ nínú ìwé àdéhùn wo̩n, pé àwo̩n ní ìgbàgbó̩ nínú ètò o̩mo̩nìyàn tó jé̩ kò‐s̩eé‐má‐nìí, ìgbàgbó̩ nínú iyì àti è̩ye̩ è̩dá ènìyàn, àti ìgbàgbó̩ nínú ìdó̩gba è̩tó̩ láàrin o̩kùnrin àti obìnrin, tó sì jé̩ pé wó̩n tún ti pinnu láti s̩e ìgbéláruge̩*_
wikipedia
yo
Bákan náà, a gbọdọ̀ rí àwọn ìgbésẹ̀ tí ó lè mú ìlọsíwájú bá orílẹ̀-èdè kan ṣoṣo tàbí àwọn orílẹ̀-èdè sí ara wọn, kí a sì rí i pé a fi owó tó jọjú wọ àwọn òfin wọ̀nyí, kí àmúlò wọn sì jẹ́ káríayé láàrín àwọn ènìyàn orílẹ̀-èdè tó jẹ́ ọmọ Àjọ-Ìṣọ̀kan Àgbáyé fúnra wọn àti láàrín àwọn ènìyàn orílẹ̀-èdè mìíràn tó wà lábẹ́ àṣẹ wọn.Abala kìínígbogbo ènìyàn ni a bí ní òmìnira; iyì àti ẹ̀tọ́ kọ̀ọ̀kan sì dọ́gba..
wikipedia
yo
Wọ́n ní ẹ̀bùn ti làákàyè àti ti ẹ̀rí-ọkàn, ó sì yẹ kí wọn ó máa hùwà sí ara wọn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìyá.Abala kejì ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ànfàní sí gbogbo ẹ̀tọ́ àti òmìnira tí a ti gbé kalẹ̀ nínú ìkéde yìí láìfi ti ọ̀rọ̀ ìyàtọ̀ ẹ̀yà kankan ṣe; ìyàtọ̀ bí i ti ẹ̀yà ènìyàn, àwọ, akọ-n̄-bábo, èdè, ẹ̀sìn, ètò ìṣèlú tàbí ìyàtọ̀ nípa èrò ẹni, orílẹ̀-èdè ẹni, orírun ẹni, ohun ìní ẹni, ibi ẹni tàbí ìyàtọ̀ mìíràn yòówù kó jẹ́..
wikipedia
yo
Síwájú sí i, a kò gbọdọ̀ ya ẹnikẹ́ni sọ́tọ̀ nítorí irú ìjọba orílẹ̀-èdè rẹ̀ ní àwùjọ àwọn orílẹ̀-èdè tàbí nítorí ètò-ìṣèlú tàbí ètò-ìdájọ́ orílẹ̀-èdè rẹ̀; orílẹ̀-èdè náà ìbáà wà ní òmìnira tàbí kí ó wà lábẹ́ ìṣàkóso ilẹ̀ mìíràn, wọn ìbáà má dáa ìjọba ara wọn ṣe tàbí kí wọ́n wà lábẹ́ ìkànì-lápá-kò yòówù tí ìbáà fẹ́ di òmìnira wọn lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè.Abala kẹ́ta ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti wà láàyè, ẹ̀tọ́ sí òmìnira àti ètò sí ààbò ara rẹ̀.Abala kẹrin a kò gbọdọ̀ mú ẹnikẹ́ni ní ẹrú tàbí kí a mú un sìn; ẹrú níní àti ó wo ẹrú ni a gbọdọ̀ fi òfin dè ní gbogbo ọ̀nà.Abala karùn-ún a kò gbọdọ̀ dá ẹni kẹ́ni lóró tàbí kí a lò ó ní ìlò ìkà tí kò yẹ ọmọ ènìyàn tàbí ìlò tó lè tàbùkù ẹ̀dá ènìyàn.Abala kẹfà ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ètò pé kí a kà á sí gẹ́gẹ́ bí ènìyàn lábẹ́ òfin ní ibi gbogbo.Abala keje gbogbo ènìyàn ló dọ́gba lábẹ́ òfin..
wikipedia
yo
Wọ́n sì ní ẹ̀tọ́ sí àá bọ́ lábẹ́ òfin láìsí ìyàsọ́tọ̀ kankan..
wikipedia
yo
Gbogbo ènìyàn ló ní ètò sí ààbò tó dọ́gba kúrò lọ́wọ́ ìyàsọ́tọ̀ yòówù tí ìbáà lòdì sí ìkéde yìí àti ètò kúrò lọ́wọ́ gbogbo ohun tó bá lè ti ènìyàn láti ṣe irú ìyàsọ́tọ̀ bẹ́ẹ̀.Abala kẹjọẹni kọ̀ọ̀kan lórílẹ̀-èdè, ló ní ẹ̀tọ́ sí àtúnṣe tó jọjú ní ilé-ẹjọ́ fún ìwà tó lòdì sí ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn, tó jẹ́ kó-ṣeé-má-nìí gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lábẹ́ òfin àti bí òfin-ìpìlẹ̀ ṣe là á sílẹ̀.Abala Kẹsàn-àná kò gbọdọ̀ ṣàdédé fi òfin mú ènìyàn tàbí kí a kàn gbé ènìyàn tì mọ́lẹ̀, tàbí kí a lé ènìyàn jáde ní ìlú láìnídìí.Abala Kẹwàá ẹnì kọ̀ọ̀kan tí a bá fi ẹ̀sùn kàn lọ ní ètò tó dọ́gba, tó sì kún, láti ṣàlàyé ara rẹ̀ ní gbangba, níwájú ilé-ẹjọ́ tí kò ṣègbé, kí wọ́n lè ṣe ìpinnu lórí ètò àti ojúṣe rẹ̀ nípa irú ẹ̀sùn ọ̀ràn dídá tí a fi kàn án.Abala Kọkànlá ẹnikẹ́ni tí a fi ẹ̀sùn kàn ni a gbọdọ̀ gbà wí pé ó jàre títí ẹbí rẹ̀ yóò fi hàn lábẹ́ òfin nípasẹ̀ ìdájọ́ tí a ṣe ní gban|gbà nínú èyí tí ẹni tí a fi ẹ̀sùn kàn yóò ti ní gbogbo ohun tí ó nílò láti fi ṣe àwíjàre ara rẹ̀.
wikipedia
yo
A kò gbọdọ̀ dá ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ fún ẹnikẹ́ni fún pé ó hu ìwà kan tàbí pé ó ṣe àwọn àfojúfò kàn nígbà tó jẹ́ pé lásìkò tí èyí ṣẹlẹ̀, irú ìwà bẹ́ẹ̀ tàbí irú àfojúfò bẹ́ẹ̀ kò lòdì sí òfin orílẹ̀-èdè ẹni náà tàbí òfin àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé mìíràn..
wikipedia
yo
Bákan náà, ìjẹníyà tí a lè fún ẹni tó dẹ́ṣẹ̀ kò gbọdọ̀ ju èyí tó wà ní imulo ní àsìkò tí ẹni náà dá ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.Abala Kejìláẹni kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ pé kí a má ṣàdédé ṣe àyo̩júràn sí ọ̀rọ̀ ìgbésí ayé rẹ̀, tàbí sí ò̩rò̩e̩bí rẹ̀ tàbí sí ọ̀rọ̀ ìdílé rẹ̀ tàbí ìwé tí a kọ sí i; a kò sì gbọdọ̀ ba iyì àti orúkọ rẹ̀ jẹ́..
wikipedia
yo
E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí ààbò lábé̩ òfin kúrò ló̩wó̩ irú àyo̩júràn tàbí ìbanijé̩ bé̩è̩.Abala kẹtàlá e̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti rìn káàkiri ní òmìnira kí ó sì fi ibi tó bá wù ú s̩e ìbùgbé láàrin orílè̩‐èdè rè̩.
wikipedia
yo
E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti kúrò lórílè̩‐èdè yòówù kó jé̩, tó fi mó̩ orílè̩‐èdè tirè̩, kí ó sì tún padà sí orílè̩‐èdè tirẹ̀ nígbà tó bá wù ú.Abala kẹrìnlá e̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti wá ààbò àti láti je̩ àn fàní ààbò yìí ní orílè̩‐èdè mìíràn nígbà tí a bá ń s̩e inúnibíni sí i.
wikipedia
yo
A kò lè lo ẹ̀tọ́ yìí fún ẹni tí a bá pè lẹ́jọ́ tó dájú nítorí ẹ ṣe tí kò jẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ìṣèlú tàbí ohun mìíràn tí ó ṣe tí kò bá ète àti ìgbékalẹ̀ Àjọ-Ìṣọ̀kan Orílẹ̀-èdè Àgbáyé mu.Abala Kẹẹ̀ẹ́dógún ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè kan.
wikipedia
yo
A kò le s̩àdédé gba è̩tó̩ jíjé̩ o̩mo̩ orílè̩‐èdè e̩ni ló̩wó̩ e̩nìké̩ni láìnídìí tàbí kí a kò̩ fún e̩nìké̩ni láti yàn láti jé̩ o̩mo̩ orílè̩‐èdè mìíràn.Abala kẹrìndínlógún tọkùnrin tobìnrin tó bá ti bàlágà ló ní è̩tó̩ láti fé̩ ara wo̩n, kí wó̩n sì dá e̩bí ti wo̩n sílè̩ láìsí ìkanilápá‐kò kankan nípa è̩yà wo̩n, tàbí orílè̩‐èdè wo̩n tàbí è̩sìn wo̩n..
wikipedia
yo
Ẹ̀tọ́ wọn dọ́gba ninu igbeyawo ìbáà jẹ́ nígbà tí wọ́n wà papọ̀ tabi lẹ́yìn tí wọ́n bá kó ara wọn.
wikipedia
yo
A kò gbọdọ̀ ṣe igbeyawo kan láìjẹ́ pé àwọn tí ó fẹ́ fẹ́ ara wọn ní òmìnira àtọkànwá tó péye láti yàn fúnra wọn.
wikipedia
yo
Ẹbí jẹ́ ìpìlẹ̀ pàtàkì àdánidá ní àwùjọ, ó sì ní ẹ̀tọ́ pé kí àwùjọ àti orílẹ̀-èdè ó dáàbò bò ó.Abala kẹtàdínlógún ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti da ohun ìní ara rẹ̀ ní tàbí láti ní in papọ̀ pẹ̀lú àwọn mìíràn.
wikipedia
yo
A kò lè s̩àdédé gba ohun ìní e̩nì kan ló̩wó̩ rè̩ láìnídìí.Abala kejìdínlógún e̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí òmìnira èrò, òmìnira è̩rí‐o̩kàn àti òmìnira e̩ sìn..
wikipedia
yo
Ètò yìí sì gbani láàyè láti pààrọ̀ ẹ̀ sin tàbí ìgbàgbọ́ ẹni..
wikipedia
yo
Ó sì fún ẹyọ ẹni kan tàbí àkójọpọ̀ ènìyàn láàyè láti ṣe ẹ̀sìn wọn àti ìgbàgbọ́ wọn bó ṣe jẹ mọ́ ti ìkọ́ni, ìṣesí, ìjọsìn àti ìmúṣẹ ohun tí wọ́n gbàgbọ́ yálà ní ìkọ̀kọ̀ tàbí ní gbangba.Abala kọ́kàndínlógúnẹni kọ̀ọ̀kan ló ní ètò sí omi nira láti ní ìmọ̀ràn tí ó wù ú, kí ó sì sọ irú ìmọ̀ràn bẹ́ẹ̀ jáde; è̩tó̩yìí gbani láàyè láti ní ìmọ̀ràn yòówù láìsí àtakò láti ọ̀dọ̀ ẹnikẹ́ni láti wádìí ọ̀rọ̀, láti gba ìmọ̀ràn lọ́dọ̀ ẹlòmíràn tàbí láti gbani níyànjú lọ́nàkọnà láìka ààlà orílẹ̀-èdè kankan kún.Abala ogún ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ sí òmìnira láti pé jọ pọ̀ àti láti dara pọ̀ mọ́ àwọn mìíràn ní àlàáfíà.
wikipedia
yo
A kò lè fi ipá mú ẹnikẹni dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ kankan.Abala kọkànlélogún ẹni kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti kópa nínú ìṣàkóso orílẹ̀-èdè rẹ̀, yálà fúnra rẹ̀ tàbí nípasẹ̀ àwọn aṣojú tí a kò fi ipa yàn.
wikipedia
yo
E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ tó dó̩gba láti s̩e is̩é̩ ìjo̩ba ní orílè̩‐èdè rè̩.
wikipedia
yo
Ìfẹ́ àwọn ènìyàn ìlú ni yóò jẹ́ òkúta ìpìlẹ̀ fún a ṣe ìjọba; a ó máa fi ìfẹ́ yìí hàn nípasẹ̀ ìbò tòótọ́ tí a ó máa dì láti ìgbà dé ìgbà, nínú èyí tí ẹnì kọ̀ọ̀kan yóò ní ẹ̀tọ́ sí ìbò kan ṣoṣo tí a dì ní ìkọ̀kọ̀ tàbí nípasẹ̀ irú ó ná ìdìbò mìíràn tí ó bá irú ìdìbò bẹ́ẹ̀ mu.Abala kejìlélógún ẹnì kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà nínú àwùjọ ló ní ẹ̀tọ́ sí ìdáàbò bò láti ọwọ́ ìjọba àti láti jẹ́ an fà ní àwọn ètò tí ó bá ọrọ̀-ajé, ìwà láwùjọ àti àṣà abínibí mu; àwọn ètò tí ó jẹ́ kò-ṣeé-má-nìí fún iyì àti ìdàgbàsókè ẹ̀dá ènìyàn, nípa akitiyan nínú orílẹ̀-èdè àti ìfo̩wó̩s̩owó̩ pọ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè ní ìbámu pẹ̀lú ètò àti ohun àlúmọ́nì orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan.Abala kẹtàlélógún ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láti ṣiṣẹ́, láti yan irú iṣẹ́ tí ó wù ú, lábẹ́ àdéhùn tí ó tọ́ tí ó sì tún rọrùn, kí ó sì ní ààbò kúrò lọ́wọ́ orúsẹ́ ṣe.
wikipedia
yo
E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti gba iye owó tí ó dó̩gba fún irú is̩é̩ kan náà, láìsí ìyàsó̩tò̩ kankan.
wikipedia
yo
E̩nì kò̩ò̩kan tí ó bá ń s̩isé̩ ní è̩tó̩ láti gba owó os̩ù tí ó tó̩ tí yóò sì tó fún òun àti e̩bí rè̩ láti gbé ayé tí ó bu iyì kún ènìyàn; a sì lè fi kún owó yìí nípasè̩ orís̩ìí àwo̩n ètò ìrànló̩wó̩ mìíràn nígbà tí ó bá yẹ.
wikipedia
yo
E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti dá e̩gbé̩ òs̩ìs̩é̩ sílè̩ àti láti dara pò̩ mó̩ irú e̩gbe̩; bé̩è̩ láti dáàbò bo àwo̩n ohun tí ó je̩ é̩ lógún.Abala ke̩rìnlélógúneni kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí ìsinmi àti fàájì pè̩lú àkókò tí kò pò̩ jù lé̩nu is̩é̩ àti àsìkò ìsinmi lé̩nu is̩é̩ láti ìgbà dé ìgbà tí a ó sanwó fún.Abala ke̩è̩é̩dó̩gbò̩n e̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ láti gbé ìgbé ayé tó bójú mu nínú èyí tí òun àti e̩bí rè̩ yóò wà ní ìlera àti àlàáfíà, tí wo̩n yóò sì ní oúnje̩, as̩o̩, ilégbèé, àti àn fàní fún ìwòsàn àti gbogbo ohun tó lè mú è̩dá gbé ìgbé ayé rere..
wikipedia
yo
Bákan náà, ẹnì kọ̀ọ̀kan lọ tún ní ààbò nígbà àìníṣẹ́lọ́wọ́, nígbà Aísá n, nígbà tó bá di aláàbọ̀-ara, ní ipò opó, nígbà ogbó rẹ̀ tabi ìgbà mìíràn tí eniyan kò ní ọ̀nà láti rí oúnjẹ óo jó, tí eléyìí kì í sì í ṣe ẹ̀bi oluwa rẹ̀.
wikipedia
yo
A ní láti pèsè ìtó̩jú àti ìrànló̩wó̩ pàtàkì fún àwo̩n abiyamo̩ àti àwo̩n o̩mo̩dé..
wikipedia
yo
Gbogbo àwọn ọmọdé yóò máa jẹ́ àwọn án fàní ààbò kan náà nínú àwùjọ yálà àwọn òbí wọn fẹ́ ara wọn ni tàbí wọn kò fẹ́ ara wọn.Abala kẹrìndínlọ́gbọ̀n..
wikipedia
yo
Ó kéré tán, ẹ̀kọ́ gbọdọ̀ jẹ́ ọ̀fẹ́ ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹ̀kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ yìí sì gbọdọ̀ jẹ́ dandan..
wikipedia
yo
A gbọdọ̀ pèsè ẹ̀kọ́ iṣẹ́-ọwọ́, àti ti ìmọ̀-ẹ̀rọ fún àwọn ènìyàn lápapọ̀..
wikipedia
yo
An fani tó dọ́gba ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga gbọdọ̀ wà ní àrọ́wọ́tó gbogbo ẹni tó bá tọ́ sí.
wikipedia
yo
Ohun tí yóo jẹ́ ète ẹ̀kọ́ ni láti mú ìlọsíwájú tó péye bá ẹ̀dá eniyan, kí ó sì túbọ̀ rí i pé àwọn eniyan bọ̀wọ̀ fún ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ati àwọn òmìnira wọn, tó jẹ́ kó-ṣeé-má-nìí..
wikipedia
yo
Ẹ tó ẹ̀kọ́ gbọdọ̀ lè rí i pé ẹ̀mí; ìgbọ́ra-ẹni-yé, ìbágbépọ̀ àlàáfíà, àti ìfẹ́ ọ̀rẹ́-sí-ọ̀rẹ́ wà láàrín orílẹ̀-èdè, láàrín ẹ̀yà kan sí òmíràn àti láàrín ẹlẹ́sìn kan sí òmíràn..
wikipedia
yo
Ẹ tọ́-ẹ̀kọ́ sì gbọdọ̀ kún àwọn akitiyan Àjọ-Ìṣọ̀kan Orílẹ̀-èdè Àgbáyé lọ́wọ́ láti rí i pé àlàáfíà fìdí múlẹ̀.
wikipedia
yo
Àwo̩n òbí ló ní è̩tó̩ tó ga jù lo̩ láti yan è̩kó̩ tí wó̩n bá fé̩ fún àwo̩n o̩mo̩ wo̩n.Abala ke̩tàdínló̩gbò̩n..
wikipedia
yo
ẹnì kọ̀ọ̀kan ló ní ẹ̀tọ́ láìjẹ́ pé a fi ipá mú un láti kópa nínú àpapọ̀ ìgbé ayé àwùjọ rẹ̀, kí ó jẹ ìgbádùn gbogbo ohun àmúṣẹ wá ibẹ̀, kí ó sì kópa nínú ìdàgbàsókè ìmọ̀ sàra sì àti àwọn àn fàní tó ń ti ibẹ̀ jáde.
wikipedia
yo
E̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí ààbò àn fàní ìmo̩yì àti ohun ìní tí ó je̩ yo̩ láti inú is̩é̩ yòówù tí ó bá s̩e ìbáà s̩e ìmò̩ sáyé̩n sì, ìwé kíko̩ tàbí is̩é̩ o̩nà.Abala kejìdínlọ́gbọ̀n e̩nì kò̩ò̩kan ló ní è̩tó̩ sí ètò nínú àwùjo̩ rè̩ àti ní gbogbo àwùjo̩ àgbáyé níbi tí àwo̩n è̩tó̩ òmìnira tí a ti gbé kalè̩ nínú ìkéde yìí yóò ti jé̩ mímús̩e̩.Abala Kọkàndínlọ́gbọ̀n e̩nì kò̩ò̩kan ló ní àwo̩n ojús̩e kan sí àwùjo̩, nípasè̩ èyí tí ó fi lè s̩eé s̩e fún e̩ni náà láti ní ìdàgbàsókè kíkún gé̩gé̩ bí è̩dá ènìyàn.
wikipedia
yo
Òfin yóò de ẹnì kọ̀ọ̀kan láti fi ọwọ́ àti ìmo̩yì tí ó tọ́ fún ẹ̀tọ́ àti òmìnira àwọn ẹlòmíràn nígbà tí ẹni náà bá ń lo àwọn ẹ̀tọ́ àti òmìnira ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Ẹ yí wa ní ìbámu pẹ̀lú ọ̀nà tó yẹ, tó sì tọ́ láti fi báni lò nínú àwùjọ fún ire àti àlàáfíà àwùjọ náà nínú èyí tí ìjọba yóò wà lọ́wọ́ gbogbo ènìyàn.
wikipedia
yo
A kò gbo̩dò̩ lo àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira wò̩nyí rárá, ní ò̩nà yòówù kó jé̩, tó bá lòdì sí àwo̩n ète àti ìgbékalè̩ Ajo̩‐àpapò̩ orílè̩‐èdè agbáyé.Abala ọgbọ́na kò gbo̩dò̩ túmò̩ ohunkóhun nínú ìkéde yìí gé̩gé̩ bí ohun tí ó fún orílè̩‐èdè kan tàbí àkójo̩pò̩ àwo̩n ènìyàn kan tàbí e̩nìké̩ni ní è̩tó̩ láti s̩e ohunkóhun tí yóò mú ìparun bá èyíkéyìí nínú àwo̩n è̩tó̩ àti òmìnira tí a kéde yìí.Àwọn ìtọ́kasí ìkéde..
wikipedia
yo
Ìlú yi ni ó jẹ́ arin-gbùngbùn fún orílẹ̀-èdè Nàíjíríà, ti ilẹ̀ Ìjọba àpapọ̀ si fìdí kalẹ̀ si ni abẹ́ aṣọ Rock, Àpáta agbára ni Abuja...
wikipedia
yo
Abuja di olu-ilu orile-ede Naijiria ni osu kejila, odun 1991, akosile eto ikaniyan ti odun 2006 so wipe Abuja ni olugbe 776, itọkasiawon ilu ati abule Naijiria ni Naijiriaoluilu ipinle oluilu oluilu ni Afrika..
wikipedia
yo
Ile-ifowopamọ Central Bank ti Nàìjíríà (CBN) nikan lo láṣẹ lati se owo sita ni orile-ede Naijiria.itan Naijiria bere si ni lo owo naira ni ojo kìíní osu kìíní odun 1973, won Pààrọ̀ Owo Yewe Naijiriati Nàìjíríà n lọ tele..
wikipedia
yo
Owó tuntun náà jẹ́ owó àkọ́kọ́ tí Nàìjíríà ṣe jáde lẹ́yìn òmìnira Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Owó ti Nàìjíríà ń lọ kí ó tó di ìgbà náà ní Ponhùn Nàìjíríà ti ìjọba a kọ́ni le Nàìjíríà ṣe ní ọdún 1959, tí orúkọ Elisabeti kejì sì wà lára rẹ̀.Obafemi Awolowo lo mu aba orúkọ “náírà” wa, o yóò lára “Nàìjíríà” sugbon , Mínísítà tí o n rí si ọrọ̀ .[3] Shehu Shagari, o gbe owó náà sita ni odun 1973. ti ọdún 1973. ti Nigeria sọ pé wọ́n gbìyànjú lati sàkóso ki sọ̀fọ̀ ki o wa sile..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2011, CBN fi kún owó-è ní ìlọ́po mẹ́fà, ó gòkè sí láti 6.25% sí 12%
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ Kkalnlọ́gbọ̀n oṣù kìíní, ọdún 2012, CBN pinnu láti ṣètọ́jú owó-èlé náà kí ó bà lé wa ní 12% àti pé kí àfikún sí ow níná bá lè dikú.Ní ọjọ́ ogún oṣù kẹfà, ọdún 2016, náírà níh ànfààní láti léfòó, lẹ́yìn tó tí wọ́n ti fi sí àhámọ́ ní n197 sí US$1 fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣù.Wàhálà tó wáyé látàrí owó Nàìjíríà tuntun ṣẹlẹ̀ lójijì ní oṣù kejì ní ọdún 2023 nítorí àìtó náírà àti ìgbìyànjú àwọn ìjọba láti mú kí àwọn ará-ìlú fi tipátipá ná owó tuntun tí wọ́n ṣe gbé jáde..
wikipedia
yo
Èyí sì já sí ìfi-ẹ̀hónú-hàn káàkiri àdúgbò ní àárín oṣù leji, ní ọdún 2023.Bákan ní ọdún 1973, wọ́n gbé koínṣì wọlé, a sì ní Koínṣì ní kọ́bọ̀ , 1, 5, 10 àti 25..
wikipedia
yo
Kounṣì àti 1 ni wọ́n ṣe Plu idẹ, wọ́n sì fi kópa ṣe àwọn owó ńlá..
wikipedia
yo
Àwọn kòínsí kọ́bọ̀ ni wọ́n ṣe sí pépà ní ọdún náà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1991, àwọn Koínṣì kékèèké bíi kọ́bọ̀ 1, 10 àti 25 ni wọ́n ṣe pẹ̀lú kópa àti ìrìn..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì, ọdún 2007, wọ́n ṣe àwọn Koínṣì tuntun síta bíi kọ́bọ̀ 50, N1 àti ₦2..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1991, wọ́n tẹ ₦50 jáde, wọ́n sì fi kóinsìn dípò kọ́bọ̀ 50 kọ́bọ̀ àti N1 ní ọdún 1991..
wikipedia
yo
Èyí sì tẹ̀lé N100 ní ọdún 1999, N200 ní 2000, N500 ní 2001 àti N1,000 ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹwàá, ọdún 2005.Ní oṣù kejì, ọdún 2007, àwọn ẹ̀yà tuntun fún n5 sì ń50 bẹ̀rẹ̀ sí ní jáde..
wikipedia
yo
Ní àárín ọdún 2009 nígbà tí Sanusi lámì Sanusi di gómìnà CBN, wọ́n sẹ́yipada àwọn n5, N10care àti ₦50 sí owó náìlòn.Hlórí owó N1,000,000, wọ́n ṣe kiní kan sí lẹ́yìn láti má fàyè ayédèrú..
wikipedia
yo
Awon abuda adamo ara owo naa ni aworan Alhaji Aliyu Mai-Bornu ati Dr..
wikipedia
yo
Clement Isong, ti wọn jọ fìgbà kan jẹ gomina CBN.Lórí ìtẹ̀jáde àkọ́kọ́ ti wọ́n ṣe fun N100 ní ọjọ́ kìíní Oṣù Kejìlá, ọdún 1999, àwòrán Àpáta Zuma, èyí tí wọ́n sọ pé ó wà ní agbègbè olú-ìlú ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà lára owó náà, àmọ́ Ìpínlẹ̀ Niger gan-an ni ó wà..
wikipedia
yo
Wọ́n padà yọ ìtọ́ka pé Abuja ní àwá yìí wá kúrò lára owó náà.Ní ọdún 2012, CBN gbèrò láti ṣatẹ̀jáde owó tuntun fún ₦5,000..
wikipedia
yo
Ile-ifowopamọ naa tun pinnu lati seyipada n5, N10, N20 ati N50 si Koinsin to ti pada di iwe bayii.Ni ojo kejila oṣu kọkanla, ọdun 2014, Central Bank of Nigeria gbero lati ṣàtúnṣe si N100 ṣàjọyọ̀ idasilẹ Naijiria fun ọgọrun-un ọdun..
wikipedia
yo