cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Agijẹ Kaduna ni Center of Learg’’ (Ilé fún E)..
wikipedia
yo
Oruko yii se Regi won nitori opo ile-eko to ni kimi ni o wa ni ipinle naa, àpẹẹrẹ ni Ahmadu Bello University.Ipinle Kaduna ode-oni je ile ìṣura fun awon ohun ìlàjú ile Afirika, kódà, Nok Civilization ti o gbérù lati c.1500 BC si c..
wikipedia
yo
Ní sétúrì 9th, Owu-wután tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ya'Qbi ṣe àkọsílẹ̀ ìwàláyé ìjọba Hausa, èyí tí ó wà kí wọ́n tó sọ ọ́ di sòkòtò Calite ní ọdún 1800 lẹ́yìn ìjà àwọn Fúlàní..
wikipedia
yo
ní àkọ́kọ́ ìmúnisìn, àwọn olùdarí ilẹ̀- Britain sọ Kaduna di olú-ìlú àbọ̀ ní àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ dídásilẹ̀ ní ọdún 1991 láti apá ìwọ̀ oòrùn Gúsù Kano, Jigawa wà ní ààlà tó wà lãrín orílẹ̀-èdè Niger àti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Dutse ni olú ìlú fún ìpínlẹ̀ náà, tí òṣìjẹ́ ìlú tí ó tóbi jùlọ ní ìpín Jigawa.Àwọn èdèàwọn oríṣiríṣi èdè tí ó wà ní ìpín Jigawa ní bádé, Warji, Duwáí..
wikipedia
yo
Hausa ati fúlà jẹ́ ede ti wọn n sọ jù ní ìpínlẹ̀ Jigawa.Ìjọba Ìbímọ Ìjọba Ìbílẹ̀ ti ó wà ní ìpínlẹ̀ Ìwówá jẹ́ mẹtadinlọgbọn..
wikipedia
yo
Augustus Meredith Adisa Akinlóyè (August 19, 1916 – September 18, 2007) jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ni 1916-Awon Ojol ni 2007awon ara Naijiria..
wikipedia
yo
Niger jẹ́ ìpínlẹ̀ kan àárín gbùngbùn apá Ariwa lórílẹ̀-èdè Nigeria..
wikipedia
yo
Wọ́n pín ìpínlẹ Niger sí agbègbè-ìṣèjọba mẹ́ta, ní ìpín A, B, D..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú ńlá mìíràn tí wọ́n wà ní Niger; Bídà, Kontara and SÚLÈJA..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìlú àwọn Ààrẹ-àná ológun, Ọ̀gágun Ibrahim Babangida àti AbdulSalami Abubakar..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn Nupe, Gbagyi, Kodeku, Kamda, Gunmàlúù, hún-saare, Hausa àti kòkun ní wọ́n pọ̀jù ní ìpínlẹ̀ náà.Orúkọ Ọ̀dọ́ Niger ni wọ́n fi sórí Ìpínlẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ náà ni odò tí wọ́n fi ń pèsè ina-ọba, Ojúdji Dam àti Shìrorò Dam, bẹ́ẹ̀ náà, ibẹ̀ ni Zúngẹ̀ru Dam wà..
wikipedia
yo
Ibe ni jebba dam ti ni ipin ni Ipinle Niger ati Ipinle Kwara..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ náà ni gurara falls, tí wọ́n fi orúkọ odò gurara sórí wa..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Nasarawa jẹ́ ìkan ninú àwọn ìpínlẹ̀ 36 ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
oluilu re ni BOFI.itan idasileIpinle Nasarawa je didadida ni ojo kinni, osu kẹwàá, odun 1996 nigba isejoba Abacha, ti won pin kuro ni Ipinle Plateau ode oni.Ijoba ibileawon ijoba ibile ti o wa ni Ipinle Nasarawa je metala..
wikipedia
yo
Abdullahi adámú - National chairman, APCṢúlèman Opú-Public Relations Praciasetọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Kano jẹ́ olú ìlú Ìpínlẹ̀ Kano ati Ìlú tí ó tóbijùlọ ẹ̀kẹ́ta ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́yìn ìlú Ìbàdàn àti ìlú Èkó..
wikipedia
yo
Awon ibi to lajú bere gba ile to tobi to 137 km ti o si ni awon ijoba ibile mefa — Kano Municipal, Faegge, Gwale, Gwale, Tararin ati Nasarawa — pelu olugbeÀpótí17,225, ni ikaniyan odun 2006.Ọ̀RỌ̀ adayeba laarin ipinle kan ipinlessiterikan & Sa-H/ giga giga gigaroko-iwe giga àkàitọkasiKano..
wikipedia
yo
Onigfú Dube ilẹ̀ South Africa ni Ṣíṣel Dube reggae ní Ṣíṣe Dube un kọ nígbà ayé Relucky Dubeolórin reggae ní South Africa kú ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kẹwàá ọdún 2007.Ìtọ́kasí Ọjọ́ìbí ní 1964àwọn ọjọ́aláìsí ní 2007àwọn olórin ará gúúsù Áfríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣẹ̀dá ìpínlẹ̀ yí látara ìpínlẹ̀ Sokoto ní ọjọ́ kẹtàbà.Oṣù Kẹjọ ọdún 1991, tí wọ́n sì sọ olú-ìlú Ìpínlẹ̀ náà ní Birmin Kebbi..
wikipedia
yo
of the 36 States of Nigeria, Kebbi is the tenth largest in area and 22nd most ipávelólo, with an estimated population of about 4.4 million as of 2016..
wikipedia
yo
Oruko inagijẹ ipinle naa a ma je ile eto (land of Elóró]] a ba ni ki a wo ile ipinle naa, ipinle yi je ile Igbo ti ojo si ma n ro nibe dara dara..
wikipedia
yo
Lára àwọn ohun tó mú ìpínlẹ̀ yí yàtọ̀ sí àwọn ìpínlẹ̀ tó yíká ni wípé oní iṣan omi odò tí ó ń bọ̀ láti ìpínlẹ̀ Sokoto tí omi náà sì ṣàn lọ sí inú Adágún Odò Ojúdjì..
wikipedia
yo
Pupọ awọn olugbe ipinlẹ ti wọn jẹ ida ọgọrin le mẹrin ni wọn je ẹlẹṣin Musulumi nigba ti awon tókù je ẹlẹṣin kristeni ati awon elesin bori.Ibi ti o di Ipinle Kebbi loni laye atijọ ni o wa labẹ iṣakoso ile ọba Kebbi ti wọn jẹ Hausa Babe State, ti ti si ibẹrẹ ọdun 1800 ki awọn ajìjà esin Fulani gba di e lara ile naa si abẹ iṣakoso ijọba Gwandu Emirate labẹ iṣakoso Sokoto fọ́nká..
wikipedia
yo
Leyin ija esin yi, awon omo ilubibibibi ti n ba awon eniyan Sokoto ja ni gbogbo igba saaju ki awon Geesi amunisin to fipa gba ile naa ti won si n ṣakoso re lati ibere 1900 titi di 1910 titi di odun 1960 ti orile-ede Naijiria gba ominira..
wikipedia
yo
.Àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ìpínlẹ̀ Kebbi ni Ìjọba ìbílẹ̀ mọ́kànlélógún àti ilẹ̀ ọba mẹrin (Gwandu, Argungu, Yarin And Zuru), Aleiro arẹwà Dandi Argungu Augie Bagudo Birn Kebbi Bunza Dandi Fakà Gwandu Jega Kalgo koko/Sse Maoba Miyagaski N Saka Shanga Keroko Wagu Yagurinàwọn Zuru Efin E Eda Efin tabi ẹka ede ti won n sọ ni Ipinle Po, amo * Hausa ni o gbaju-gbaja julọ julọ..
wikipedia
yo
Àwọn èdè míràn tí wọ́n tún ń sọ níbẹ̀ ní èdè Fulfulde, ut-hùn, àti Sorkọ́.Ìpínlẹ̀ Kebbi gẹ́gẹ́ bi àwọn Ìpínlẹ̀ tókù ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n ń lo Gómìnà, ilé Ìgbìmọ̀ asòfin..
wikipedia
yo
àwọn ohun àlùmọ́nì ìpínlẹ̀ Kebbi ni àwọn ohun àlùmọ́nì oriṣiriṣi ti ó lè mú ìdàgbà-sókè bá ilú àti àwọn èniyàn ibẹ̀..
wikipedia
yo
Karl Heinrich Marx (May 5, 1818 – March 14, 1883) jẹ́ ara Jemani amòye, àṣeoró-okòwò olóṣèlú, akọìtàn, ìránjìnlẹ̀ olóṣèlú, Akúnjú-àwùjọ, àti Anísàlẹ̀ti Alajidìde, tí àwọn ìròọkàn rẹ̀ kó ipa pàtàkì nínú ìdàgbàsókè iṣẹ́kínnísti àti ìṣẹ́gdíẹ̀ òdeòní..
wikipedia
yo
Tíọ́rì Soṣíọ́lọ́jì tó tẹ̀lé ìlànà àti èrò Karl Marx kì í ṣe tíọ́rì òní, ó ti pẹ́ tí ó ti dáyé..
wikipedia
yo
Orúkọ rẹ̀ ni àwọn abẹnugan tíọ́rì náà fi ń pe ìlànà wọn..
wikipedia
yo
Láti nǹkan bí ọdún 1840 ni Karl Marx fúnra rẹ̀ ti ṣe ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé lórí àwùjọ àti àṣà, ṣùgbọ́n ní nǹkan bí sétúrì Ògún ni tíọ́rì náà búrẹ́kẹ láwùjọ àwọn akadá.Tíọ́rì Ìṣègbèfábo ojú-ìwé 40-52..
wikipedia
yo
Tíọ́rì tí a pè ní Ìṣègbèfábo lédè Yorùbá ní èdè Gẹ̀ẹ́sì pé ní “Femisípò"
wikipedia
yo
Láti inú èdè latínì ní èdè Gẹ̀ẹ́sì ti yá ọ̀rọ̀ náà lo ́èyí "Ìgb/ ó túmọ̀ sí ohun gbogbo tó jẹ mọ́ àbò tàbí àwọn obìnrin..
wikipedia
yo
Tíọ́rì asàtakò ìmúnisìn jẹ́ tíọ́rì lítíréṣọ̀ àkọ́kọ́ tó kanlẹ̀ wá fún lámèyítọ́ lítíréṣọ̀ àwọn orílẹ̀ èdè tó ti fojú gbọ́òru iná ìjọba amúnisìn tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Yorùbá bọ̀, wọ́n ní, abíni tún bini, abẹ́rẹ́ tún béèrè ni kì í jẹ́ ká a pe àbúrò ẹni lọ́mọ ẹni, gbogbo àwọn tíọ́rì liteso tí a ti tọ́ka sí tàbí ṣe àlàyé rẹ̀ tẹ́lẹ̀ bí ìfojúààtò-wo, ìfojú-ìhun-wò títí ó fi dé tíọ́rì MaKíṣìí kò kanlẹ̀ Wa fún lámèyítọ́ lítíréṣọ̀ àwọn adúláwọ̀ tàbí àwọn orílẹ̀ èdè tí kì í ṣe ara Yúróòpù àwọn onímọ̀ kan wulẹ̀ ń ra tíọ́rì náà bọ lítíréṣọ̀ adúláwọ̀ lọ́rùn lásán ni.Ìṣàmúlò tíọ́rì lítíréṣọ̀ mélòó kan ojú-ìwé 58-104..
wikipedia
yo
Ṣíṣe àmúlò tíọ́rì fún lámèyítọ́ iṣẹ́ ọnà aláwòmọ́ lítíréṣọ̀ ṣe pàtàkì lóde òní..
wikipedia
yo
LÁMÈYÍTỌ́ TÍ KÒ BÁ LO TÍỌ́RÌ KAN pàtó FÚN IṢẸ́ RẸ̀ KÒ NÍ ÌPÌLẸ̀ TÓ DÚRÓ LÉ..
wikipedia
yo
Irú iṣẹ́ bẹ́ẹ̀ kò sí ni wo àjọ àwọn onímọ̀ lámèyítọ́, kò sí ibi tí a kò ti lè lo tíọ́rì fún àlàyé tàbí ìgbélé-wọn iṣẹ́, ewì, eré-oníṣe tàbí eré-onítàn ìtàn àròsọ tí ó fi kan eré inú fíìmú àgbéléwò tàbí alágbèéká.Tíọ́rì ìfojú-àṣà-ìbílẹ̀-wo ojú-ìwé 25–26..
wikipedia
yo
Àwọn agbátẹrù tíọ́rì yìí sọ pé iṣẹ́ ti liteso máa ń ṣe ni láti dáàbò bo àṣà àti ìṣẹ̀ṣe àwùjọ kan, nítorí náà ohun tó gbọdọ̀ jẹ́ lámèyítọ́ lógún ní ṣíṣe àfihàn irú àwọn àṣà tó súyọ nínú iṣẹ́ ọnà aláwòmọ́ lítíréṣọ̀..
wikipedia
yo
Tíọ́rì mìíràn tí ó tún ṣe pàtàkì ni tíọ́rì tí o ń sọ̀rọ̀ nípa ìtàn ìgbésí ayé òǹkọ̀wé..
wikipedia
yo
Ohun tí tíọ́rì yìí sọ niyà e láti ṣe àtúpalẹ̀ iṣẹ́ ọnà kan, ó ṣe pàtàkì láti mọ irú ẹni tí ó ṣe náà, ìtàn ìgbésí ayé rẹ̀ àti àwọn nkan mìíràn tó kó ipa pàtàkì kí ẹni náà tó dáwọ́ lé iṣẹ́ náà àti ohun tí ó mú kí ó gbé iṣẹ́ náà gba ìlànà tí ó gbé e gbà.Tíọ́rì ìfojú-ìmọ̀-ìbára-ẹni-gbé-pọ̀-wò-lítíréṣọ̀ tàbí Soṣíọ́lọ́jì litesọ ojú-ìwé 29-35..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ tí a pè ní Soṣíọ́lọ́jì litiro jẹ́ ọ̀rọ̀ tí onímọ̀ èrò ìjìnlẹ̀ kan tí a ń pè ní Ogunàti ọmọ orílẹ̀ èdè Faransé rò fúnra rẹ̀..
wikipedia
yo
Ète láti sọ àgbéyẹ̀wò iṣẹ́ ọnà dàbí ti ìmọ̀ Sáyẹ́ńsì ló fa ìṣẹ̀dá Soṣíọ́lọ́jì lítíréṣọ̀..
wikipedia
yo
Ìmọ̀ tuntun sì lọ jẹ́ lagbooloe ẹkọ́ nípa iṣẹ́ ọnà.iwe tí a ̀wo ̀wo kéè Adeyemi (2006) TÍỌ́RÌ ní èdè Yorùbá s S'ìyẹ she Yobioti, Ijebu-Ode, Nigeria- ISBN978; ISBN978-4-15. Àwọn Ọjọ́ìbí ni 1818 ni Technology ní 1883 ní pípé ará Jemani..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó ṣẹ̀dá ohun tí a ń pè ní yìnbọnstic Theology..
wikipedia
yo
Ìlú Ile-Ife jẹ́ ìlú tí oriṣa Baba ṣìgìdì tí mo fẹ́ sọ ìtàn rẹ̀ ti wá..
wikipedia
yo
Eyi lo mu mi ya bara lati sọ ni ṣókí nipa itan isedale ilu ile-Ife..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ló ti wà lórí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ìlú Ilé-Ifẹ̀ bẹ́ẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn òǹkọ̀wé àti Onpìtàn ló ti fi èrò wọn hàn lórí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ìlú Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀jọ̀gbọ́n Bíòku (1955) dábàá wí pé a dá ìlú Ilé-Ifẹ̀ sílẹ̀ láàrín ọ̀rúndún keje àti ìkẹjọ (Seventh & Ealáìlẹ́bi Centuries)..
wikipedia
yo
Ìwòye àwọn méjèèjì fi ìmọ̀ ṣọ̀kan pé Ilé-Ifẹ̀ jẹ́ ilẹ̀ kan gbòógì láàárín ọ̀rúndún keje sí ìkejìlá (Seventh tó Twenth Centuries) àti pé Ilé-Ifẹ̀ ti wà ní ìletò kékèèkée tẹ́lẹ̀ rí kó tó di pé ó wá para pọ̀ di odidi tí ó wà lónìí yìí..
wikipedia
yo
Ninu ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nu wo pẹlu Olóyè Ọbadiôrí, o ni itan Yorùbá bẹrẹ lati Ile-Ife gẹgẹ bi orisun..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí a fi ń pe “Ilé-Ifẹ̀ ní ìlú ibi tí ó jùmọ̀ ti ń mọ wá” lékèé gbogbo rẹ̀, ọ̀nà mẹrin pataki nípa ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ Ilé-Ifẹ̀ ni àwọn ònkọ̀tàn ti kọ sílẹ̀ tí wọ́n sì gbe yẹ̀wò..
wikipedia
yo
Nígbà tí ìtàn kejì sọ fún wa pé Odùduwà àti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ kúrò láti ìlú Mẹ́kà..
wikipedia
yo
Nínú ìrìnàjò wọn, olúkúlùkù bẹ̀rẹ̀ sí níí tẹ̀dó sí ojú ọ̀nà, nínú èyí tí kókóbiri ni òkè ọya wà..
wikipedia
yo
Odùduwà kó àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ lọ́pon de ilè-Ifẹ̀ ní ìgbẹ̀yìngbẹ́yín..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ sì ni Odùduwà bá àwọn àgbà awo ní Ilé-Ifẹ̀ tí Odùduwà sì ja ìjà ajáborí tí ó sì borí lọ́wọ́ wọn..
wikipedia
yo
Ero keta yii je ero Eluyemi ti o je omo bibi ilu ile-Ife, o gba pe ila oorun ti awon eniyan n tọka si gege bi orisun Yoruba ni "Òkè-ọrá..
wikipedia
yo
Òkè ọ̀rá ni ilẹ̀ tí ó lọ́ràá tí Odùduwà ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ rí láti fi dáko, wọ́n sì gba ilẹ̀ náà lọ́wọ́ àwọn ẹni tí wọ́n bá níbẹ̀..
wikipedia
yo
Kí Odùduwà tó wáyé àti kí ìlú Ilé-Ifẹ̀ tó fìdí múlẹ̀ ní àwọn ìletò mẹ́tàlá ti wà káàkiri agbègbè náà tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì ní baálẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ìletò mẹtala yìí ló para pọ̀ di ìletò ọ̀kan ṣoṣo tí ọ̀kọ̀ọ̀kan baálé àwọn ìletò wọnyi sì ń ṣe olùdarí àpapọ̀ lóòrèkóòrè..
wikipedia
yo
Ohun tí ó ṣe pàtàkì ni pé púpọ̀ nínú àwọn orúkọ wọ̀nyìí ló sì wà títí di òní gẹ́gẹ́ bí àdúgbò tàbí agbègbè lábẹ́ Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀rànfẹ́ baálé òkè ọ̀rá ni ó kọ́kọ́ ṣe baálé àpapọ̀ ìletò wọ̀nyí nígbà tí Ọbàtálá ṣe Baálẹ̀ tó gbẹ́yìn..
wikipedia
yo
Ní àkótán, gbogbo èrò mẹ́rẹ̀ẹ̀rin tí mo ti mẹ́nu bà ní ṣókí náà ló sọ nípa ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ìlú Ilẹ̀-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Nínú èrò tèmi, ní àfikún, ìtàn àtẹnudẹ́nu ni ìtàn àwọn ara ilé-Ifẹ̀ ó kún fún ẹ̀kọ́ àti àṣà, bí ó ti wù kí ó rí ó yẹ kí a sọ pé irú ìtàn bẹ́ẹ̀ kọ́ ni àkọsílẹ̀ ṣùgbọ́n ó jẹ́ ìjìnlẹ̀ ìtàn..
wikipedia
yo
Ọ̀nà tí a lè pín àwọn òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá síẹnu kò kò lórí iye àwọn òrìṣà tó wà nílẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Bí àwọn kan ṣe sọ pé ọ̀kànlénígba òrìṣà ló wà ní ààfin Ọọ̀ni bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn kan ń sọ pé irinwó òrìṣà ó le ọ̀kan (401 deities) ló wà lóde Ìmo a o lè sọ pàtó iye òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá tó wà pẹ̀lú iye òrìṣà tí a ti mẹ́nu bà lókè yìí, nítorí pé kì í ṣe gbogbo òrìṣà tó rọ̀ láti òde-ọ̀run wa sí òde-ìsàmo ni a ń pè ní òrìṣà..
wikipedia
yo
A rí àwọn abàmì nǹkan mìíràn tí àwọn eniyan sọ di oriṣa..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ a sì rí àwọn alágbára àtijọ́ tí a sọ di ẹni òrìṣà èyí tí òrìṣà baba ṣìgìdì tí ìwádìí yìí dá lé lórí wa..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú gbogbo àlàyé wọ̀nyìí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ onímọ̀ ló ti gbìyànjú láti pín òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá sí oríṣiìrìranìté ọ̀nà..
wikipedia
yo
Àwọn kan pín in sí ọ̀nà méjì, àwọn kan pín in sí ọ̀nà mẹrin..
wikipedia
yo
Bákan náà ni a tún rí àwọn kan tí wọ́n pín òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá sí ọ̀nà márùn-ún..
wikipedia
yo
Àwọn wọ̀nyí ní òrìṣà tó fi ẹ̀wọ̀n rọ láti ìsálú ọ̀run ró sí òde-idin..
wikipedia
yo
Àwọn tí a sọ di oriṣa lẹ́yìn ikú wọn nítorí ohun ribiribi tí wọn gbé ṣe nígbà ayé wọn..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ ni àwọn òrìṣà bíi Agẹmọ, Yemọja, Mọ́remí, olùorógbó, Loán, Agán, bàbá ṣìgìdì, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àwọn tí wọ́n wà ní ìsọ̀rí kẹta yí ni àwọn ẹ̀mí àìrí bíi iwin, ẹbọra, ati ọrọ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ni àwọn òrìṣà àtẹ̀wọ̀nrọ bíi Odùduwà, Ṣàngó, Ọya, èṣù àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
àwọn ni àwọn ọmọ tí a sọ di òrìṣà nítorí ibi tí a bí wọn..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn àgbéyẹ̀wò iṣẹ́ tí àwọn ènìyàn kan ti ṣe lóríi ọ̀nà tí a lè gbà pín àwọn òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá, nínú ẹ̀rọ tèmi, pínpín òrìṣà sí ìsọ̀rí mẹ́rin ni mo fara mọ́ nítorí ìsọ̀rí yìí ló ṣàlàyé fínnífínní gbogbo nǹkan tí a kà sí òrìṣà nílẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Adewole (supervisor)àwọn ìtọ́kasí òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ìfáàrà "Ẹ toko máa wá ìjọba óṣèlú ná èyí tókù a ó sì fi fún yìnàpilẹ̀kọ yìí ṣe àgbéyẹ̀wò ìbáṣepọ̀ láàrín Áfíríkà (Yorùbá) àti ètò ìṣèjọba ní Latin America, àti ní pàtàkì jùlọ bí wọ́n ṣe ìgbógun tí àwọn ènìyàn Afirika nípa kíkópa nínú ìṣèjọba Latin Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Nígbà tí Brazil yóò dúró gẹ́gẹ́ bíi burẹ̀ fún Ṣíṣe àlàyé ní orin bíbí Afró-Brazilian ni a ó maa fìwé́ àwọn ohun tí ó ṣẹlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Afka-Latin America nípa ètò ìṣèjọba àti igbesi ayé wọn ni ayé àtijọ àti ayé ode oni.iṣẹ́ yìí yóò yiri bí àwọn ènìyàn ilẹ̀ Áfíríkà ti ṣe pé́lé àpé òmọ̀ àti òṣèlú ibi tí wọ́n bá ara wọn..
wikipedia
yo
Ìbéèrè ni pé ń jẹ́ ìgbé ayé àwọn ènìyàn ilẹ̀ adúláwọ̀ ní orílẹ̀ èdè Latin America dábòbò àṣà àti ìṣe wọn láti ẹ̀yìn wá bí? Tàbí ó mú kí àyípadà ó dé bá àjọṣepọ̀ wọn?Nígbà tí a bá sọ̀rọ̀ nípa Áfíríkà ní àsìkò òwò ẹrú, Yorùbá jẹ́ ẹ̀yà kan pàtàkì tí àṣà àti ìṣe wọn borí tó sì gbajúmọ̀ jù láàrín àwọn ẹ̀yà ilẹ̀ Áfíríkà yòókù..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ gbogbo àṣà àti ìṣe Yorùbá bíi ẹ̀sìn, ìbọ̀rìṣà àti ìgbàgbọ́ wọn ni wọ́n mú ní ọ̀kúnkúndùn ní òkè òkun níbi tí wọ́n kó wọn lọ gẹ́gẹ́ bíi ẹrù..
wikipedia
yo
Èyí kìí ṣe àsọdùn rárá pé kàkà kí kìnnìún ṣe akápò ẹkùn, oníkálùkù yóò ṣe ọdẹ tirẹ̀ lọ́tọ̀ọ̀tọ̀..
wikipedia
yo
Nítorí náà a rí àwọn ẹrú tí wọ́n gbà pé àwọn yóó máa ṣe àṣà àti ẹ̀sìn wọn bí àwọn tí ń ṣe nígbà tí wọ́n wà ní Áfíríkà, àwọn ẹrú tí wọ́n gbà pé wọn kò ní ṣe àṣà àti ẹ̀sìn ìlú aláwọ̀ funfun ni wọ́n pàgọ́ (CAdomble) tí Yorùbá sì jẹ́ aṣáájú fún àwọn yòókù.Ohun tí à ń sọ ni pé kàkà tí Yorùbá yóò fi faramọ́ àṣà, ẹ̀sìn àti iṣẹ́ ibi tí wọ́n bá ara wọn, ẹ̀sìn àti àṣà tí wọ́n ní wọ́n gbé lárugẹ tí ó sì gbilẹ̀ débi pé àwọn ẹ̀yà Áfíríkà mìíràn darapọ̀ mọ́ wọn tí wọ́n sì jọ ń bọ àwọn òrìṣà bíi ẹ̀là, ogun, Ṣàngó, Ọbàtálá, ṣànpọ̀nná, Ọbalúfọ̀n àti àwọn irúnmọlẹ̀ yòókù ní òkè òkun..
wikipedia
yo
Afro-Latin America ni àwọn ẹrú lati ilẹ̀ Afirika tí wọ́n kó wọn gba Amerika lo si Gúsù Amẹrika (South American) ní àwọn ilú bíi..
wikipedia
yo
Ìyàtọ̀ tí ó wà láàrín Afro-America àti Afro-Latin America ni pé wọ́n kò gba àwọn dúdú (Áfíríkà) láàyè láti ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn aláwọ̀ funfun (Òyìnbó) ní Afro-America, ṣùgbọ́n kò sí ẹlẹ́yà-mẹ̀yà ní Afro-Latin America.Ìṣòro mìíràn tí ó tún kojú àwọn ènìyàn Áfíríkà ní èdè, ní Afro-America, èdè ìṣèjọba wọn ní èdè Gẹ̀ẹ́sì (English) ṣùgbọ́n èyí kò rí bẹ́ẹ̀ ní Afro-Latin America, èdè ìṣèjọba ní èdè Faransé, Potogí àti Spanish (French, Pèrèodò and Spanish)..
wikipedia
yo
Èyí mú kí ó ṣòro fún àwọn ènìyàn láti ní ìbáṣepọ̀ tàbí ìfikùnlukùn àyàfi kí wọn ó rí ògbufọ̀..
wikipedia
yo
Títí di ọdún 1970 sí 1972 ní Brazil ó jẹ́ ìṣòro fún àwọn ènìyàn tí ó ń ṣe akọ̀ròyìn láti kọ́ nǹkan nípa Áfíríkà.Àwọn ìṣòro mìíràn tí ó tún kojú àwọn ènìyàn Áfíríkà ní Àríwá Amẹ́ríkà n títà kò àti ìkórira àwọn dúdú gbogbo ohun tí kò bá ti dára wọ́n gbà pé owó Áfíríkà ló ti wá..
wikipedia
yo
Wọn kò gbà ki àwọn Afirika ni Aṣojú ninú ètò Òṣèlú àti Ìjọba, bakan naa ni wọn kò ni ètò òṣèlú àti ìjọba, bakan náà ni wọn kò ni ẹ̀tọ́ lati dibò tàbi díje fún ipò kankan..
wikipedia
yo
Bí ìgbógun ti àwọn adúláwọ̀ àti ìwà elẹ́yàmẹyà ṣe nípọn tó..
wikipedia
yo
Síbẹ̀, àwọn ènìyàn Áfíríkà ṣì rí ara wọn gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà kannã, ibi yòówù kí wọn ó wà, ìṣòro yòówù kí wọn ó máa là kọjá..
wikipedia
yo
Bí gbogbo ìṣòro tí ó ń kojú àwọn Áfíríkà ṣe pọ̀ tó yìí, ipa tí àwọn tí ó wà ní ìpàgọ́ kò ṣe fi ọwọ́ rọ́ sẹ́yìn, ní oṣù kínní ọdún 1976 àwọn ẹgbẹ́ tí ó wà ní ìpàgọ́ ní Bahia kò gba ìwé àṣẹ láti ọ̀dọ̀ àwọn ọlọ́pàá kí wọ́n tó ṣe ìpàdé tàbí ìwọ́de.Bákan náà ni Colombia, ní agbègbè Caribbean (àwọn ẹrú tí wọ́n sá) ni wọ́n pàgọ́ síbẹ̀, àwọn Palenquenos kò tijú láti fi ara wọn hàn gẹ́gẹ́ bí Áfíríkà nípa ìgbé ayé wọn títí di òní.Bákan náà ni a kò lè ṣàì mẹ́nu bá ipa ribiribi tí Manuel Zapeta Ollivella ti ṣe oníṣègùn, òpìtàn àti òǹkọ̀wé ọmọ Afro - Colombian kọ, láti ìgbà tí ó ti wà ní akẹ́kọ̀ọ́ ni ó ti fi ìfẹ́ hàn sí ìjàgbara àwọn ènìyàn ilẹ̀ Afirika lọ́wọ́ àwọn amúnisìn..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1950 ó kópa nínú Ìwọ́de ìta gbangba tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Afro-Colombian University ṣe láti tako ìwà amúnisìn..
wikipedia
yo
Ọmọ rẹ̀ obìnrin tí ó jẹ́ ọ̀dọ́ Elúlú náà kọ ewì lórí àwọn adúláwọ̀..
wikipedia
yo
Nígandes Santa Cruz tí ó jẹ́ ọmọ Peru ní ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ nǹkan nípa ìṣòro tí ó ń kojú àwọn ènìyàn adúláwọ̀ tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní "Congo libre" tí ó fi sórí Patrice lummbá..
wikipedia
yo