cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Nínú ìwé tí ó kọ ni ó ṣe àfihàn ìbáṣepọ̀ tó wà láàrín Áfíríkà àti Peru..
wikipedia
yo
O sọ ninu iwe rẹ ogbon ti awon alawo funfun n da lati mu àdínkù ba awon Afirika ati bi won o se..
wikipedia
yo
Dín agbára wọn kù, ó fi ìwé rẹ̀ náà tako ìwà elẹ́yàmẹyà.A ò ní kógo já bí a bá kùnà láti mẹ́nuba abDias do Nascijà tí òun náà kọ́ ìwé lórí Afro-Latin America, iṣẹ́ òǹkọ̀wé yìí ni ó gbégbá orókè láàrin àwọn òǹkọ̀wé Afro-Brazilian.ìgúnlẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ìbáṣepọ̀ láàrín adúláwọ̀ àti funfun dàbí ọmọ ọ̀dọ̀ sí ọ̀gá rẹ̀ (olówó rẹ̀) ṣùgbọ́n kò pé kò jìnnà, ìfarakinra nípa igbeyawo , ẹ̀sìn bẹ̀rẹ̀ sí ní dá àwọn méjèèjì papọ̀.Àsẹ̀yìnwá, àsẹ̀yìnbọ̀ ìkọlura àti ìfagagbága àṣà bẹ̀rẹ̀ sí ní kó ara wọn jọ wọ́n ń dá ẹgbẹ́ sílẹ̀ tí a mọ̀ sí ẹgbẹ́ ajìjàgbara lọ́wọ́ amúnisìn..
wikipedia
yo
Àwọn dúdú bẹ̀rẹ̀ sí ní rí ara wọn gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan láìwo ẹ̀yà tàbí ìlú tàbí gbé òṣùnwọ̀n lé bí ìyà ti ń jẹ wọ́n sí.Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé ìjàgbara láti kópa nínú ìṣèjọba wáyé, ṣùgbọ́n kò so èso rere..
wikipedia
yo
Ni ọdún 1920 àwọn Aláwọ̀dúdú dá ẹgbẹ́ Òṣèlú ti wọn silẹ̀ ni orílẹ̀ èdè Brazil UruGay àti Cuba..
wikipedia
yo
Ní orílẹ̀ èdè Brazil ni a ti dá ẹgbẹ́ tí a pè ní frente Negra Brasiláì (BrazilBrazil Front) wọ́n forúkọ ẹgbẹ́ náà sílẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn elétò ìdìbò gẹ́gẹ́ bí ẹgbẹ́ òṣèlú, ṣùgbọ́n ìjákulẹ̀ dé báa ìgbésẹ̀ yìí látàrí ìfipá gba ìjọba ológun lọ́wọ́ ìjọba Láẹ̀sẹ̀ tó wáyé..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ẹgbẹ́ náà tún bẹ̀rẹ̀ ìpàdé wọn ṣùgbọ́n ojú àpá kò jọ ojú ara nítorí pé ìpàdé yìí kò lọ́wọ́ òṣèlú nínú bíi ti tẹ́lẹ̀.Láàrín ọdún 1973 – 5 ni àwọn àyípadà díẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní dé bá àwọn adúláwọ̀ tí ó wà lábẹ́ ìjọba Brazil..
wikipedia
yo
Gbígba òmìnira orílẹ̀-èdè Guinea-Bissau Mozambique àti Angol kò ṣàì lọ́wọ́ ipa tí orílẹ̀ - èdè Brazil kó nínú..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ipa tí Brazil kó nípa èdè àti àṣà Áfíríkà kìí ṣe kèrémí..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn Angola ni wọ́n ń ṣe àtìpó ní Brazil.Ìwé ìtọ́kasí anan ddzienyo (African Yorùbá) Culture and the Political Kingdom in Latin America..
wikipedia
yo
Mohandas KaramChand Gandhi (Ọjọ́ ìbí 2 October, 1869 – 30 January, 1948) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ indiaitọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1869àwọn Ojoaláìsí ní 1948àwọn ará India..
wikipedia
yo
Ohun ní Orílẹ̀-èdè Keje Títóbi Jùlọ gẹ́gẹ́ bí ìtóbi jẹ́ografi, orílẹ̀-èdè kìn-ín-ní tó ní iye àwọn ènìyàn jùlọ pẹ̀lú bíi 1.43 bilionu ènìyàn, àti ìjọba-Oníbò tó ní iye àwọn ènìyàn jùlọ lágbà..
wikipedia
yo
O ja mo òkun India ní gúúsù, òkun Lárúbáwá ní ìwọ̀ oòrùn, àti ẹ̀bádò benga ní ìlà oòrùn, India ní etíkun tó jẹ́ 7,16.6 ayeraye (4,700 Mis)..
wikipedia
yo
O ní ààlà láàrín Pakistan ní ìwọ̀ oòrùn; Ṣáínà, Nepal, àti Bhu sí àríwá; àti Bangladeshi àti Burma ní ìlà oòrùn..
wikipedia
yo
India wà nitosi Sri Lanka, àti MalDives tí wọ́n wà ní Òkun India.Gẹ́gẹ́ bíi ilẹ̀ ọ̀làjú Àfonífojì Indus jẹ́ ibi tó ní ìdàgbàsókè púpọ̀, abẹ́orílẹ̀ India jẹ́ ibi àwọn ènìyàn mọ̀ fún ọ̀la àti asà rẹ̀ káàkiri ayé..
wikipedia
yo
Esin nlá mẹ́rin, Hinduism, Buddhism, Jainism ati sikhism ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ látibẹ̀, nígbàtí Zororismriphile, ẹ̀sìn jù, ẹ̀sìn Krístì àti Ìmàle dé síbẹ̀ ní Ẹgbẹ̀rúndún Àkókó IO (CE) wọ́n sì kópa nínú bi orísirísi àṣà agbègbè nã lẹ́té..
wikipedia
yo
Díẹ̀díẹ̀ ó jẹ́ fífàmọ́ látọwọ́ British East India company láti ìbẹ̀rẹ̀ ará ìkejìdínlógún, ó sì di ilé àmúsìn ilé-ọba ìsọdọ̀kan láti àrin ọ̀rúndún ìkàndínlógún, India di orílẹ̀-èdè alómìnira ní 1947 lẹ́yìn akitiyan fún ìsọtima tó ṣe pàtàkì fún isàtako aláìṣẹ̀ jàgídíjàgan kákiri.India jẹ́ orílẹ̀-èdè Olómìnira kan tó ní ìpínlẹ̀ 28 àti àwọn agbègbè ìṣọ̀kan méje pẹ̀lú sístemu onílé òṣèlúaralú..
wikipedia
yo
Okòwò India ni okòwò ìkọkànlá títóbijùlọ gẹ́gẹ́ bí ọlọ́wẹjó Gd lagbaye àti ìkẹrin títóbijùlọ gẹ́gẹ́ bi ìbámu agbára ìrajà
wikipedia
yo
Ótún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ àjọni àwọn orílẹ̀-èdè, G-20, Bric, SAFTA àti àgbájọ ọwọ́ Àgbáyé..
wikipedia
yo
India jẹ́ orílẹ̀-èdè tóní ohun-ìjagun bombu inúMU, ó sì ní ilé-iṣẹ́ ológun gbàdúràẹ ton náwójùlọ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ ológun adigun kejì títóbijùlọ lágbà..
wikipedia
yo
Àtúnṣe okòwò tó bẹ̀rẹ̀ láti 1991 ti sọ India di ìkan nínú àwọn okòwò tó ń dàgbà kíákíá jùlọ lágbà; síbẹ̀síbẹ̀, àìní sì tún bá jà, àìmọ̀ọ́kọ, ìwà-ìbàjẹ́-ìbàjẹ́, àrùn, àti àìjẹunkánú..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí àwùjọ ẹ̀sìn ọlọpọlọpọ, ẹlẹ́dẹ̀púpọ̀ àti ẹlẹ́yà ènìyàn púpọ̀, India tún jẹ́ ibùgbé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹran-ìgbẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ibi aláàbò.Orísun ìtumọ̀ ọrọ̀ India ránkà gẹ́gẹ́ bí orúkọ wa láti Indus, tó wá láti ọrọ̀ Persia àtijọ́ Híńdù, láti sánkọ́wọ́ Sinnílẹ̀ SinDhu, orúkọ ìbílẹ̀ fún odò Indus..
wikipedia
yo
Àwọn ggbìmọ̀ ayéijọ́un ń pe àwọn ara India ní indoi (indoi), àwọn ènìyàn Indus..
wikipedia
yo
Ìlànà Ìbágbépọ̀ Ilẹ̀ India àti Lílo Ọ̀rọ̀ Donepọ̀ nínú ọ̀pọ̀ àwọn èdè India bákannã tún ṣeìdámọ̀ BHarat (pípè ) gẹ́gẹ́ bí orúkọ oníbiṣẹ́ irú kanna..
wikipedia
yo
Bharat gege bi oruko wa lati oruko oba olokiki kẹfàté ninu awon itan-awa Hindu..
wikipedia
yo
Hindustan (), ní bérébéré tó jẹ́ ọ̀rọ̀ Persia fún "Ilẹ̀ Hindus" láti tọ́ka sí àparíú India, bákannã tún lílọ gẹ́gẹ́ bí orúkọ gbogbo India.Ìtàn àwọn ibùgbé àpáta ìgbà òkúta pẹ̀lú àwọn ìyàwòrán ní Bhimbetka Rock Shelters ní madHya Pradesh ní ẹ̀rí igbe ènìyàn pípéjùlọ ní India..
wikipedia
yo
Àwọn ibùdó àkọ́kọ́ tí a mọ̀ bẹ̀rẹ̀ ní ọdún tó ju 9,000 sẹ́yìn lọ, díẹ̀díẹ̀ ó sì dàgbà sókè sí Indus valley Civilisation, tí ọjọ́ orí rẹ̀ tó ọdún 3400 BCE ní apáòrùn India..
wikipedia
yo
Eyi jẹ́ títẹ̀lé pẹ̀lú Vedi Period, tó ṣe ìpilẹ̀ṣẹ̀ ẹ̀sìn Hindu àti àwọn àṣà míràn ìgbà Ìbẹ̀rẹ̀ Àwùjọ India, ó sì parí ní àwọn ọdún 500 BCE..
wikipedia
yo
Láti bí 550 BC, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé-Ọba a*'já àti orílẹ̀-èdè ìtòsí tí a mọ̀ bí Mahaètò jẹ́ dídásílẹ̀ kákiri ibè.ní ọ̀rúndún kẹta kí (BC), ọ̀pọ̀ gbogbo gúúsù Asia jẹ́ òfàpọ̀ di ilé Maur ma ìràru *"Gupta Maurya ó sí díkọ́ ní àsìkò àkọ́kọ́..
wikipedia
yo
Láti ìgbà ìlú kẹta ìọ́ (CE), ìjọba ìran Gupta sáris ìgbà tí a mọ̀ bí bí "ìgbà ìgúngún India Aùnùn àwọn ilédúróò ní apágúùsù India jẹ́ kíjá gbogbo àwọn tí UnifásíLu] tí ní Origa àti ti “yàn Empire..
wikipedia
yo
Sayẹn, Tladoloji, Iṣẹ-ẹrọ, Iṣẹ-ọna, ogbon, Ede, Litireso, Matheikuìkì, itoràwọ̀, Esin ati Imọ-oye di olókùnkùn Labẹ Itọju Awọn Ọba wọnyi.leyin awon iborile lati arin Asia larin orundun 10th ati 12th, opo ariwa India ni won bo si abe ijoba Delhi Sultanate ati leyin eyi waye ileỌbalúaye Mughal..
wikipedia
yo
Lábẹ́ Ìṣèjọba AkBar the Great, India gbádùn ìdàgbàsókè àṣà àti okòwò púpọ̀ àti ìrẹ́pọ̀ ẹ̀sìn..
wikipedia
yo
Àwọn Ọbalúayé Mughal díẹ̀díẹ̀ fẹ́ ilẹ̀ wọn sí púpọ̀ láti dórí apá ńlá abẹ́orílẹ̀..
wikipedia
yo
Sibẹsibẹ, ní àríwá-apá-ọ̀run India, alágbára tó jọba ibẹ̀ ni Ilẹ̀ọba Ahom ti Assam, gẹ́gẹ́ bí ikan ninu àwọn Ilẹ̀ọba tí wọ́n lòdì sí ìjọbalẹ́nilórí Mughal..
wikipedia
yo
ihamọ́ níńlá àkọ́kọ́ sí agbára ìjọba Mughal wá látọ̀dọ̀ ọba Hindu Rajput kan Maha Rana PTap ti Towa ní orundun 16th ati leyin eyi Látọ̀dọ̀ orílẹ̀-èdè Hindu kan tó ń jẹ́ Adapapọ̀ Maratha, tó joba lori òpó India ní arin orundun 18th.Lati orundun 16th, awon alagbara ará Europe bi Portugal, Hollándì, Fránsì, àti Ìparapọ̀ Ilẹ̀ọba ṣe ìdásílẹ̀ ibudo Owo (trading posts) bẹ síni lẹ́yìn èyí Wọ́n lo anfani tí àwọn ìjà Abẹ́lé ibẹ̀ fa wa láti ṣẹ̀dásílẹ̀ àwọn ibiàmúsìn níbẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tó fi di 1856, ọ̀pọ̀ India ti bọ́ sábẹ́ ìdarí British East India company..
wikipedia
yo
Ọdún kan lẹ́yìn èyí, ìgbógundi kãkiri àwọn ẹyọ ológun olódi ìjọba àti àwọn Ilẹ̀ọba, tí a mọ̀ bí ogún ìlòlọ́mọ àkọ́kọ́ India tàbí ìrọ́jáde mútiny, kojú ìdarí ilé-iṣẹ́ yí gidigidi ṣùgbọ́n kò yọrí sí rere..
wikipedia
yo
Nitori Àìdúrórégé, India bọ́ sí abẹ́ ìṣèìṣèjọba tààrà Ọba Alade Britani.Ni orundun 20th, akitiyan fun Ìlọway kakiri orile-ede bẹrẹ latọwọ Indian National Congress ati àwọn àgbájọ olóṣèlú míràn..
wikipedia
yo
Olórí India lílòma Gandhi léwájú àwọn ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbésẹ̀ torílẹ̀-èdè fún Àìgbọràn aráàlú Àìní-jàgídíjàgan ..
wikipedia
yo
Ni ojo 15 osu kejo 1947, India gba Olaàádọ́rin kuro lọ́wọ́ ìṣèjọba Britani, sugbon nigba kanna awon agbegbe ogunlọgọ Musulum jẹ pipin lati da orile-ede otooto Pakistan..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ 26 òṣì kinní 1950, India di orílẹ̀-èdè olómìnira bẹ́ síni ìlànà ìbágbépọ̀ tuntun jẹ́ gbígbé jáde.Láti ìgbà ìlọlọ́mọ, India ti ní àwọn ìṣòro láti owójàgídíjàgan ẹ̀sìn, Casteism, naxalism, ìṣèdanilọ́rọ̀ àti látọwọ́ àwọn ìgbógunti olùdáṣe agbègbè, àgàgà ní jáḿmú àti Kalísh àti àríwáila India..
wikipedia
yo
Láti igba àwọn ọdún 1990 àwọn ìdìgbòlù adánilóró ti nípa lórí ọpọlọpọ àwọn ìlú India..
wikipedia
yo
India ni ariyanjiyan ile pẹlu orile-ede olominira awon eniyan ilẹ̀ Ṣáínà, to di ni ọdun 1962 Ogun Ṣáínà-India, ati pẹlu Pakistan, to fa awon ogun ni 1947, 1965, 1971 ati ni 1999..
wikipedia
yo
India je omo egbe Adasile Ìparapọ̀ awon orile-ede (gege bi India Britani) ati Non-Gned Movement..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1974, India ṣe jiclear Test nípamọ́ ati idanwo marun ni 1998, eyi sọ India di orile-ede to ni bombu inutọ́..
wikipedia
yo
Láti 1991, atúnsẹ̀sẹ̀ okòwò pàtàkì ti sọ India di ìkan nínú àwọn okòwò tó ń dàgbà kíákíá jùlọ lágbàyé, èyí fún lágbára púpọ̀ láyé.Ìjọba ìlànà-ìbágbépọ̀ ilẹ̀ India, tó jẹ́ ìlànà-ìbágbépọ̀ tógun àti tó kúnrẹ́rẹ́jùlọ ti orílẹ̀-èdè alómìnira lágbà, jẹ́ gbígbà bí òfin ní 26 January 1950..
wikipedia
yo
Àkókò-sọ ìlànà-ìbágbépọ̀ yí ṣètumọ̀ India gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè Olómìnira Toṣèlúq Sovereààtò, SosiaòwòÁmósì, ti Araayé..
wikipedia
yo
India ni iléaṣòfin oníyẹ̀wùmeji tó ń ṣiṣẹ́ bí Sísste onílé irú irú Westminster..
wikipedia
yo
Irú ìjọba rẹ̀ jẹ́ jíjúwe pé ó jẹ́ bí ‘aṣi-Federal’ pẹ̀lú Gbọ̀ngán tó lágbára àti àwọn ìpínlẹ̀ tí wọn kò lágbára, ṣùgbọ́n ó ti di àpapọ̀ díẹ̀díẹ̀ láti òpin àwọn ọdún 1990 nítorí àwọn ìyípadà olóṣèlú, olókòwò àti aláwùjọ.Ààrẹ ilẹ̀ India ni olórí orílẹ̀-èdè tó jẹ́ Ydídí látọwọ́ Ìgbìmọ̀ Ìdìbò fún ìgbà ọdún márún kan..
wikipedia
yo
Alakoso agba ni olori ijọba, ohun lo si ṣẹ̀gbéṣe ọpọ agbara alaṣẹ..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí yíyan látọwọ́ Ààrẹ,Alakoso àgbà jẹ́ Titileyin latọwọ ẹgbẹ́ oloselu tabi ifowosowopo oloselu to ni ogunlọgọ àwọn ijoko ni ile kekere ileaṣofin..
wikipedia
yo
Apá ìjọba apàṣẹ ni Ààrẹ, igbákejì Ààrẹ, àti Ìgbìmọ̀ Àwọn Alakoso (Aladi ni Igbimọ apàṣẹ rẹ) tí Olórí rẹ̀ jẹ́ Alakoso Àgbà..
wikipedia
yo
Alakoso yiowu to ni ipo gbọ́dọ̀ jẹ ikan ninu àwọn ọmọ ile ileaṣofin..
wikipedia
yo
Ninu Siste onile ti India, apàṣẹ wà lábẹ́ aṣòfin, níbi tí Alakoso Àgbà Àgbà ìgbìmọ̀ rẹ̀ wà lábẹ́ ilẹ̀ kékeré.Aṣòfin ilẹ̀ India ní Iléaṣòfin oníwúméjì, tó ní ilẹ̀ òkè tí ó n jẹ́ Rajya Cereyen (Ìgbìmọ̀ àwọn ìpínlẹ̀) àti ilẹ̀ kékeré tó ń jẹ́ lọ Sabta (Ilé àwọn ènìyàn)..
wikipedia
yo
Rajya Sabha, agbárajo àìyẹsẹ̀, ní 245 ọmọ ẹgbẹ́ tí wọ́n wà níbẹ̀ fún ọdún marun..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ wọn jẹ́ dídìbòyán tààrà látọwọ́ àwọn aṣòfin ìpínlẹ̀ àti agbègbè gẹ́gẹ́ bí iye àwọn ènìyàn wọn.Àwọn ìpínlẹ̀ indiàìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ Òṣèlú Olómìnira ti Puerto ríkò jẹ egbe oselu ni orile-ede PU Rico...
wikipedia
yo
ìpínlẹ̀ ṣòkòtò jẹ́ ikan ninu àwọn ìpínlẹ̀ mẹrindilogun ti ó wà ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Sokoto wa ni àríwá iwọ oorun Naijiria orukọ gomina ipinlẹ Sokoto lọwọlọwọ bayii ni arakunrin Tanbuwalijọba ibileawon ijoba ibile ti o wa ni ipinlẹ Sokoto jẹ mẹtalelogun..
wikipedia
yo
Pupọ àwọn olùgbé rẹ ni mumúyè, Fúlàní, Jẹ́njo, Wabekum, àti àwọn ẹ̀yà kọ́nà tí wọ́n gbilẹ̀ jùlọ apá àríwá ìpínlẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Nigbati Jukun, Chamba, Tiv, Dokub ati radar ti wọn ṣawari pe wọn gbilẹ julọ ni apa guusu ipinlẹ naa..
wikipedia
yo
àárín Gọ́gọ́tà ìpínlẹ̀ náà ni ó kún jùlọ fún àwọn ènìyàn Mambìlà, Chamba, Fúlàní àti Jibáwa..
wikipedia
yo
Ó lé ní oríṣi ẹ̀yà mẹ́tàdínlọ́gọ́rin, àti àwọn èdè wọn ní ìpínlẹ̀ Taraba.Ìtàn ìpínlẹ̀ náà ni wọ́n dá sílẹ̀ látara ìpínlẹ̀ gọngọlá tẹ́lẹ̀ rí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1991, látọwọ́ ìjọba ológun tí Ọ̀gágun Ibrahim Babangida.Geography ìpínlẹ̀ Taraba ní ìsopọ̀ ní ìwọ̀ Oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ Nasarawa àti ìpínlẹ̀ Benue, ní àríwá ìwọ̀ oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ Plateau,ní àríwá pẹ̀lú ìpínlẹ̀ Bauchi àti ìpínlẹ̀ Gombe,ní àríwá-ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ adáwà, àti sí gúúsù pẹ̀lú agbègbè àríwá ìwọ̀ oòrùn ní Cameroon.Àwọn Benue, pínlẹ́sẹ̀, Taraba àti ibi ní àwọn odò ní ìpínlẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe wá láti àwọn orí-òkè Cameroon, tí ó fẹ́ ẹ san gba gbogbo ìpínlẹ̀ náà ní àríwá àti gúúsù tààrà lọ inú River Niger.Àwọn ẹkùn ìjọba ìbílẹ̀ ìpínlẹ̀ Taraba Sabenu àwọn ẹkùn ìjọba ìbílẹ̀ merindinlogunlgas)..
wikipedia
yo
Èdè lódedínlógún Èdè mìíràn tí wọ́n sọ ní Ìpínlẹ̀ Taraba nìwọ̀nyí akum, Ṣónwen, Embi, Fiya of Bis, Dakoko, MRep, Tha, Yaniuse, Yotti, Ywo.Àwọn àwòrán èèyàn jàǹkànjàǹkàn jàǹkànjàǹkàn Aisha yéyé Jud-Hassan (Mama Taraba) – Mínísítà fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, aṣojú ilé Ìgbìmọ̀-Aṣòfin fún ẹkùn Ariwa Taraba Taraba Emmanuel Bv - aṣojú Ilé Ìgbìmọ̀-Aṣòfin fún ẹkùn gúúsù Taraba, Igbákejì apàṣẹ aṣojú Ilé Ìgbìmọ̀-Aṣòfin Theophilus Danjuma – Ọmọ-ogun orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, òṣèlú, Oroko, Ọ̀gágun àgbà ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (1975-1979), Mínísítà fún ètò abo (1999-2003) dari Isus Israyath – Gómìnà Taraba lọ́ọ́lọ́ọ́ Àwòránh Mamman, Mínísítà fún ina-Eọgọ́ta ní orílẹ̀- èdè Nàìjíríà mah Mohammed Mohammed- Adájọ́ Àgbà fún orílẹ̀ èdè Nàìjíríà Joly Nyame – Gómìnà ìpínlẹ̀ Taraba South Dan sun – Gómìnà ìpínlẹ̀ Taraba Taraba Yusuf Abubakar Yusuf – aṣojú Gbogbo San Ilé-Aṣòfin Fún sẹnti Taraba Taraba, Ọmọ ẹgbẹ́ Ọmọlẹ́yìn “All Progressive Congress(APC/ibùgbé/ Convention nni Committee (CECP) Shu Isa Isa [ aṣojú- Amíràn Ilé Ìgbìmọ̀-Aṣòfin fún ẹkùn Ariwa Àríwá Taraba Lo Nigun Ni Post Office- with map- with L
wikipedia
yo
Ipinle Yobe jẹ ọkan ninu àwọn ipinle mẹrindinlogoji ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ipinle Yobe jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ni agbègbè àríwá-ila-oorun orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ti o pin ààlà pẹlu ìpínlẹ̀ Borno..
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹtàdínlọrọ oṣù kẹjọ ọdún 1991 ni wọ́n dá sílẹ̀..
wikipedia
yo
Damaturu jẹ́ òlùlù ìpínlẹ̀ Yobe.Ìrísí ìpínlẹ̀ náààwọn ìpínlẹ̀ ti Yobe múlẹ̀ tii ni Bauchi, Borno, Gombe, àti Jigawa..
wikipedia
yo
Ipinle Yobe wa ni gbongbo Ariwa diìrètí ati agbegbe Zader ti òlùlù Niger.Ìtàn idasilẹìpínlẹ̀ Yobe jẹ didasilẹ̀ ni ọjọ Ketaloogbon, oṣu kejo, ọdun 1991 nigba isejoba Babangida..
wikipedia
yo
Ipinle Yobe jẹ didasilẹ̀ nitoripe ipinle Borno Agbanna tobi julati bojútó, ti o si mu ki wọn yọ Ipinle Yobe lara rẹ.Ijoba Ibileawon ijoba ibile ti o wa ni Ipinle Yobe jẹ metadinlogun..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Zamfara jẹ́ ikan nínu àwọn ìpínlẹ̀ 36 ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn agbègbè ìjọba ìpínlẹ̀ Zamfara Zamfara ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́rìnlá.Ilé ẹ̀kọ́ gígaFederal Polytechnic, Kaura-na-mọdázam State UniversityFederal University Gusau College of Education (Technicalàìlè), Gusau State College of Art and Sciences, Gusau State College of Education, Maruàwọn èèyàn jàǹkànjàǹkànAisha Madawakí Matawalle Abdul'Aziz Abubakar yarí Ahmad Sani Yerikaìtọ́ka Poisos Poisoning kills in Nigeria..
wikipedia
yo
Ọdún tódọ́gba jẹ́ ọdún lẹ́nda tó ní ọjọ́ kan le láti bá jẹ́ kí ọdún lẹ́nda ó ní ìbámu pọ̀ mọ́ igba ọdún.2008 tódọ́gba..
wikipedia
yo
A máa ń gbé fíìmù jáde nígbà tí a bá gba àwòrán àwọn ènìyàn àti àwọn nǹkan sílẹ̀ pẹ̀lú kámẹ́rà, tàbí tí a bá ṣẹ̀dá àwòrán nǹkan nípa lílo àwọn irinṣẹ́ kọ̀mpútà..
wikipedia
yo
A maa n lo fiimu lati ṣẹ̀fẹ̀, lati da àwọn ènìyàn lára yá, gẹ́gẹ́ bi irinṣẹ́ nla ti a fi n kọ́ àwọn ará ìlú ní nǹkan tuntun..
wikipedia
yo
To use a camera to record a story or real events so that it can be shown in the cinema or on Television.(itan tí a so pèlú ohùn àti àwòrán tí ó dúró sójú kan, tí a gbé síta fún wíwò ní sinimá tàbí lóríi tẹlifísàn fún ìdálárayá... tí a fi ẹ̀rọ ìwolórí sílẹ̀ kámẹ́rà gba ìtàn tàbí ìṣẹ̀lẹ̀ ojú ayé sílẹ̀ kí a ba à le gbé síta fún wíwò ní sinimá tàbí lórí tẹlifísànohun tí ó ṣe kókó ni wí pé ìtàn ni fiimu máa ń sọ pẹ̀lú àwòrán àwọn òṣèré lóríṣìíríṣìí..
wikipedia
yo
Ẹ̀rọ Kámẹ́rà ni wọ́n máa ń lò láti gba àwọn àwòrán yìí sílẹ̀.Oríṣìíríṣìí fíìmù tó wáoríṣìíríṣìí fíìmù ni ó wà..
wikipedia
yo
Àwọn tí ó níí ṣe pẹ̀lú ìtàn ìwáṣẹ̀ tàbí àwọn ìtàn akọni..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ àwọn Fíímù àgbéléwò tí ó wà lábẹ́ owó yìí, tí wọ́n sì ti gbé jáde ni; jogún-ò-mí, Odùduwà, Ẹfúnṣetán Aníwúrà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.A tún ní àwọn kan tí wọ́n níí ṣe pẹ̀lú Hiwu ìwà ọ̀daràn..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ àwọn fíìmú tí ó ti wà lórí igbá tí ó sì wà lábẹ́ owó yìí ni; Tombọ̀lọ̀, ìKaba àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ fiimu ti o níí se pẹlu Efe ni won ti gbe jade..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ ni fíìmù bàbá Latin, onsere kan tí ó gbajúmọ̀ nínu fíìmù Yorùbá tí ó pè ní, “Mr President" tàbí èyí tí òṣèré inú fíìmù òyìnjá ní ilé Naijaria kan tí a n pè ní Nkem Owoh ṣe..
wikipedia
yo
Ó pè é ní “Oṣùà in London”.Owó kẹrin ni èyí tí wọ́n ń pè ní “Drama Films” (Fifíìmù orí ìtàgé)..
wikipedia
yo
Orí ìtàgé ni wọ́n ti kọ́kọ́ máa ń ṣe irú eré báyìí kí wọ́n tó gbé jáde sínú kásétí..
wikipedia
yo
Yàtọ̀ sí èyí, a tún rí àwọn tí wọ́n máa ń ṣẹ̀ láti ba àwọn eniyan lẹ́rù..
wikipedia
yo
Nínú irú fíìmú yìí, a o ó máa rí oríṣi nǹkan tí yóò ba ènìyàn lẹ́rù bíi iwin olórí mẹ́fà, ki ilẹ̀ dédé lanu gbé ènìyàn kan ṣoṣo mi láàárín ọjà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ irúfẹ́ fíìmù wọ̀nyí ni Aníkúlápó ti Ìyá Rainbow òṣèré Yorùbá kan gbé jáde..
wikipedia
yo
Irúfẹ́ fíìmù yìí ni wọ́n ń pè ní “Horror Films” lédè Òyìnbó..
wikipedia
yo
Bákan náà ni a ní a tún rí àwọn tí wọn ń pè ní “Dance and Musical Film” (Oní)..
wikipedia
yo
A tun ni awọn miiran bii Science Fiction (Merìírí ti Sayẹn), Action Film (oníjàgídíjàgan) ati Rabo films (itan lori iwadii) ti ko tii bẹrẹ lọdọ wa nibi.Awon akoonu fiimu ninu awọn fiimu ti o n jade ni orile ede Naijiria lo ni akoonu ti o nii se pẹlu iṣoro ti o n koju awọn mùtúmùwà ile Afirika..
wikipedia
yo
Àwọn fíìmù kan máa ń gbé ẹ̀sìn Kírísítẹ́nì àti Mùsùlùmí lẹ́sẹ̀ nígbà tí àwọn kan ń polongo ìhìnrere..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ irú àwọn fíìmú wọ̀nyí nií “agbára ńlá” tí Mike bámiloyè ṣe, “Pomi àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Yàtò sí àwọn fíìmú tí ò níí ṣe pẹ̀lú ẹ̀sìn lóríṣiṣiri, a tún ní àwọn tí ò níí ṣe pẹ̀lú ìdàrúdàpọ̀ tí ó maa ń ṣẹlẹ̀ nígbà tí àwọn tí ó níí ṣẹ̀ pẹ̀lú ìdàrúdàpọ̀ tí ó máa ń ṣẹlẹ̀ nígbà tí àwọn ẹsin méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ bá kọlu ara wọn, yálà nígbà tí àwọn ọmọ wọn bá fẹ́ láti fẹ́ ara wọn tàbí nígbà tí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ bá dà wọ́n pọ̀..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ ni fiimu kan tí wọ́n pè ní “Not Without My Daughter (Láìsí Ọmọbinrin Mi) ti o n sọ itan nipa ọkunrin Musulumi kan ati obinrin Kírísítẹ́nì kan tí wọ́n fẹ́ ṣe ìgbéyàwó tí wọ́n sì tún rí oríṣi ìṣòro nígbà tí wọ́n ń gbáradì fún ìgbéyàwó wọn.Bákan náà, àwọn fiimu kan tún wà tí iṣẹ́ pàtàkì tí wọ́n ń jẹ́ níí ṣe pẹ̀lú àrùn tí ó bá ń kojú àwùjọ lásìkò kan kì í ṣe ní Afrika nìkan ni irú fíìmú yìí ti ń jáde..
wikipedia
yo
Ni ile Amerika, a ri fiimu kan ti won pe ni "philadebidi"
wikipedia
yo
Pataki ohun tí o jẹ́ akoonu fiimu yìí ni bi awọn eniyan ṣe maa n huwa si awọn ti o ni arun Éèdì..
wikipedia
yo
Ní ilẹ̀ Nàìjíríà náà, a rí irú fíìmù bíi "Elebọ̀lọ̀" (Charlot) àti "WHOpẹ́ of Change" (tíko ìyípadà) tí ó nií ṣe pẹ̀lú àrùn kópapọ̀ éèdì. sí i, àwọn àkóónú mìíràn tí fíìmù tún maá n ní ní ìwà ìjẹ́, Ìkìlọ̀ lórí bí wọ́n ṣe máa ń kọ́ iyán àwọn obìnrin ilẹ̀ Áfríkà kéré, ikilọ nípa àṣà òkèèrè tí ó kú kan àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. YORÙ (viii tí ó kọ́kọ́ jáde jáde máa fi àṣà Yorùbá hàn sí gbogbo àgbáyé nítorí wí pé àwọn tí wọ́n ń ṣe fíìmù nígbà náà gbà wí pé ọ̀nà kan tí àwọn le gbà láti jẹ́ kí àwọn ará ará òkèèrè ó gba fíìmù Yorùbá gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ tí ó kúnjú òṣùwọ̀n ní láti fi àṣà àti iṣẹ́ wa hàn nínú eré náà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1975 ọ̀la balógun gbé fíìmù kan tí ó pè ní “Àjàní Ògùn”
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, àwọn díẹ̀ nínú àwọn tí ń ṣe eré ìbílẹ̀ káàkiri bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa nínú owó fiimu..
wikipedia
yo
Lásìkò yìí ni Herbert Ogundé ṣe fíìmù tí ó pè ní "Aiyé"
wikipedia
yo
Ohun kan soso ti ko wa je ki fiimu yii di itẹwọgba kaakiri ni pe, o fi awon Yoruba han gege bi eniyan burúkú ti won maa n se laarin egbe ti o n baniyan leru..
wikipedia
yo
Yàtò sí èyí, owó tí olóyè ògúndé fi ṣe fíìmù yìí fẹ́ẹ̀ lè má pé nígbà tí wọ́n tà á tán..
wikipedia
yo