cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Yorùbá bọ̀ wọ́n ní erin ó yàtọ̀ títí ó dd o ìlú Èèbó, bẹ́ẹ̀ ni jákèjádò ilẹ̀ Yorùbá kọ́ sí ibi tí wọ́n kọ́ ti mọ ogun sí òrìṣà pàtàkì tí wọ́n sì ń fi ìgbàgbọ́ wọn hàn nínú agbára rẹ̀, nípa bíbọ òrìṣà yìí àti fífi ohun tí ó tọ́ àti tí ó yẹ fún un.Oúnjẹ tí ogún aláró fẹ́ràn àti èèwọ̀ òrìṣà yìí ojú-ìwé 23-27..
wikipedia
yo
Oríṣìíríṣìí òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá ló ní oúnjẹ tirẹ̀ tí ó fẹ́ràn..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ àmàlà àti gbẹ̀gìrì ni oúnjẹ Ṣàngó, epo àti iyọ̀ ni oúnjẹ Eṣú..
wikipedia
yo
Ṣugbọn ogun ni tirẹ̀ agìrìigba (ajá) ẹmu ìkọ̀sẹ̀s, àkùkọ adìyẹ, atọrọ (Omi tútù)Ile aro ati ohun tí ó wà ní ojúbọ rẹ̀ ojú-ìwé 28–30..
wikipedia
yo
Yorùbá bọ̀ wọn ni “Ogun dé ilé-arọ ó jọba ní ilẹ̀ - aré, ogun yá ní ìre, ó mẹ́mu ní ilú ire”
wikipedia
yo
Ọrọ̀ ati ilé-ajé ni wọ́n ma ń ṣe ní ìlú ìjẹlé, èyí tí ó ṣe pataki ju ti àwọn ọmọ ìlú nílé lóko máa ń péjú ṣe ní ọdún ogún aláró..
wikipedia
yo
Ìwádìí tí mo ṣe fi hàn pé oṣù keje tàbí ìkẹjọ ni wọ́n máa ń bọ òrìṣà yìí.Ọjọ́ ọdún gan-an ojú-ìwé 38–41..
wikipedia
yo
Ní kùtù hàì ọjọ́ ọdún gan an ni àwọn ọmọ ìlú lọkunrin lobinrin yóo ti jí lọ sí ọ̀dọ̀ Olú-Aro lọ kí i fún ọdún, kí wọ́n sì gbadura fún wí pé kí ó ṣe ọpọlọpọ ọdún láyé..
wikipedia
yo
Bí wọ́n bá ti ṣe èyí tán ni wọn yóo pada sí inú ilẹ̀ wọn láti lọ gbáradì fún àwọn àlejò wọn tí yóo máa wọ ìlú wá bá wọn ṣe ọdún.Bí ogún ní ọjọ́ ọdún ojú-ìwé 41–55.Bí ogún Àjọbo ṣe wà fún gbogbo ọmọ ìlú, ni àwọn ìdílé kọ̀ọ̀kan ní ogun tí wọ́n tí wọn ń bọ̀ ní ọjọ́ náà..
wikipedia
yo
Mo Ẹ̀sìnjíhìnẹ gba ohun sílẹ̀ nínú ìwúre tí àwọn ìdílé ọ̀nàbọ̀b ṣe ní ọjọ́ ọdún náà..
wikipedia
yo
Ní àìkọ ní fi ìgbà kan bọ ìkan nínú, bí gbogbo òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá ti ní oríkì tí wọ́n fi ń kí wọn kí orí wọn sì wú láti ṣe ohun tí ẹni náà ń fẹ́ ní òrìṣà aláre náà ní tirẹ̀ ní ìlú ìjẹlé..
wikipedia
yo
Bí ogún sí ṣe ṣe pàtàkì sí ni a máa ń gbọ́ nínú oríkì rẹ̀ ní àkókò ọdún rẹ̀.Kókó inú oríkì ogun aláró tí a kó jọ (a) jíjúbà ojú-ìwé 58-59..
wikipedia
yo
Oríṣìíríṣìí kókó ni wọ́n mẹ́nu bà nínú oríkì òrìṣà yìí..
wikipedia
yo
Kò sì sí ètò kan pàtó tí wọ́n ń tẹ̀ lé lórí èwo ni yóo ṣiwaju ati èyí tí yóo tẹ̀ lé e..
wikipedia
yo
Ibà jíju yìí máa ń wáyé nígbà tí wọ́n bá kọ́kọ́ kọ igba ètò orin ọdún síta tí wọn yóò máa kọ kiri ní àdúgbò kọ̀ọ̀kan ní ìlú.(b)Ìtàn ojú-ìwé 59-60..
wikipedia
yo
Ninu oríkì ogún oríṣìíríṣìí ìtàn ni ó máa ń jẹ jáde níbẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn ìtàn yìí sì máa ń sọ nípa ìwà agbára tàbí nǹkan tí ogun ti gbé ṣe ní ìgbà ayé rẹ̀..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ nínú àkójọpọ̀ oríkì ogun aláró wọ́n mẹ́nu bà wí pé òun ni “Ṣàngó” ní ìlà Kẹtàdínláàádóje ìwúré kejì àti ìlà kìíní nínú ìwúre ìyá àfin Adévthid.(ìwú) ojú-ìwé 60-62..
wikipedia
yo
ÌWÚRE JẸ́ Ọ̀NÀ KAN PÀTÀKÌ TÍ ÀWỌN ARÁ ÌLÚ FI MÁA Ń tọrọ NǸKAN TÍ WỌ́N Ń FẸ́ LỌ́WỌ́ OGUN NÍYÀẸ̀ NÍ ÀSÌKÒ ỌDÚN RẸ̀..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ àwọn tí òrìṣà yìí ti ṣe lọ́rẹ kan tàbí òmíràn yóò wá san ẹ̀jẹ́ tí wọ́n ti jẹ́ fún un.(Ẹ)ìbẹ̀rù tí wọ́n ní fún ogun aláró ojú-ìwé 62-68.Rug a bọ wọ́n ní bí ọmọdé bá dé ibi ẹrú, ó yẹ kí ẹ̀rù bà á..
wikipedia
yo
Yàtọ̀ sí oríkì tí wọ́n máa ń kí òrìṣà yìí láti fi agbára rẹ̀ hàn bákan náà ni wọ́n tún ń bẹ̀rù rẹ̀ nítorí akọni òrìṣà ni..
wikipedia
yo
Department of African languages and Literatures, Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University, Ilé-Ifẹ̀...
wikipedia
yo
Joseph Òkèhan Ọdúnjọ jẹ́ Olùkọ̀wé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà:“Wíw Apalawọ́ ti di ìlúmọ̀míkání báyìí; ó ti gbayì ní ilé; ó ti gbayì lóko bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti gba iyì ní ìdálẹ̀ ju ilé lọ..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ òyìnbó ni ó ti fi ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ lítíréṣọ̀ adúláwọ̀ gboyè ìjìnlẹ̀ ìwé, púpọ̀ nínú àwọn ọmọ adúláwọ̀ ló sì ti di olówó àti olórúkọ nípa fífi èdè àjòjì bí èdè Gẹ̀ẹ́sì kọ ìwé lítíréṣọ̀ adúláwọ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ àkọ́sọ ó ti tó ọdún mẹ́ẹ̀dógún (láti 1970) tí mo ti ń ṣiṣẹ́ ìwádìí nípa àwọn ìwé kíkà fún alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Eni tí ó bá ẹran ẹẹ̀rìnlórí àtẹ, kò lè mọyì ẹẹ́lé, ni ọ̀rọ̀ ìtàn-àròsọ Yorùbá jẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lóde òní..
wikipedia
yo
Nígbà tí a bá sì wọ orí àtẹ lọ́jọ́ òní tí a lè tọ́ka sí ìwé ìtàn-àròsọ ogun, ọgbọ̀n tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, tí à ń sà, tí a rò, tí a ń sọ pé a fẹ́ràn ọ̀kan tàbí a yan ọ̀kan ní ìpọ̀sì, nítorí pé wọ́n wà ní..
wikipedia
yo
Èyí nìkan kí ọ̀nà tí àwa òǹkàwé òde-òní fi máa ń yunra.Ìkó tí a yẹ̀wòàti o..
wikipedia
yo
Ọlátúnjí (1988) Ìdàgbàsókè Ẹ̀kọ́ Ìmọ̀ Ìjìnlẹ̀ Yorùbá (Ọdúnjọ Memorial Lecture series)..
wikipedia
yo
Odunjo (2001) ọmọ òkú ọrun Ìbàdàn; African Universities Press ISBN978-148-148-2..2..
wikipedia
yo
Davis)Alaga, gbogbo ẹ̀yin ofòòkùn, iyì nla ni fún mi lati wà ní ìjókòó lónìí lati sọ̀rọ̀ lórí 'ìlàjú Yorùbábọ́rọ̀
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo ṣiṣẹ́ rí ní ọgbà Fásitì Ìbàdàn, n kò rò wí pé mo yẹ ní ẹ̀mí tí ó le máa ka àpilẹ̀kọ lórí ọ̀rọ̀ ìlàjú Yorùbá, mo lè ti ṣe àwọn ìwádìí ti ó jẹ mọ́ àkòrí yìí Lóòótọ́ fún àwọn àkókò kan..
wikipedia
yo
Bí a bá fi ojú inú wo ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú àwa àtọ̀húnrìnwá ni a tí ń ṣe ìwádìí orírun wa dé ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ oníwàdìí ìjìnlẹ̀ ni wọ́n kọ ìpàkọ́ sí ìwádìí òpin ọ̀rọ̀ ẹrú ní ilẹ̀ Brazil bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé gbogbo ọgbọ́n àlùmọ̀kọ́rọ́yí àti agídí paraku lórí owó ni ó mú àwọn ẹlẹ́nuugboro dìde láti máa tako òwò ẹrú ní ilẹ̀ Brazil..
wikipedia
yo
A gbọ́dọ̀ mọ̀ láti ilẹ̀ wí pé àti dúdú àti funfun ni wọ́n jọ pa owó pọ̀ gbé ogun ti òwò ẹrú ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ni kò fi ara mọ́ àtakò yìí..
wikipedia
yo
Ọ̀kan nínú àwọn tí ó tako owó ẹrú yìí jẹ́ ọmọ Yorùbá ilẹ̀ Brazil kan..
wikipedia
yo
Kán-tẹnuẹ ni baba olówó ẹrú wọ inú óofíìsì agbẹjọ́rò ọ̀rẹ́ ẹ̀ rẹ̀ yìí tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í bèèrè lọ́wọ́ ẹrú yìí, ìdí tí ó fi fẹ́ fi òun sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ó sọ síwájú wí pé òun ń tẹ́ ẹ lọ́rùn àti wí pé kò yẹ kí ó ba inújẹ́ rárá níwọ̀n ìgbà tí òun ti ń ṣe bíi baba fún-un..
wikipedia
yo
Ní tòótọ́ ẹrú yìí ń rí ìtọ́jú kò sì sí ìdí fún-un láti kún rárá, ìdí nìyí tí ẹrú yìí kò fi rí àtakò kankan fún ọ̀rọ̀ olówó rẹ̀ yìí..
wikipedia
yo
Láàrin rògbòdìyàn ni a sọ wọ́n di eruku, tí ó bá sì di ọjọ́ iwájú àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n yóò kọ nípa wọn sí àwùjọ àwọn ìràwọ̀ àti àwọn oòrùn..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn kò sì ṣe bẹ́ẹ̀ kọ àkọsílẹ̀ àwọn ènìyàn dúdú tí ó ní owó nínú owó ẹrùu rẹ̀, ìwọ̀nba èyí tí a sì rí ni ó wá láti ọ̀dọ̀ aláwọ̀ funfun àti wí pé ìwọ̀nba péréte ni àwọn aláwọ̀ dúdú tí a kọ àkọsílẹ̀ wọn.Àwọn aláwọ̀ funfun kò kọ́ ibi ara sí ọ̀rọ̀ Luiz gámà, wọ́n kìí sì ṣáábà fọn rere rẹ̀ rárá ṣùgbọ́n ìrìn-àjò rẹ̀ láti ẹrú lásán di olókìkí ènìyàn ni ó yẹ kí a kó ibi ara sí ju bí a ti ṣe yìí lọ..
wikipedia
yo
Abala méjì ni ó wú mi lórí jù nínú ìgbé ayé gámà; àkọ́kọ́ ni dídàgbà rẹ̀ nínú òfíì àti ọ̀láà..
wikipedia
yo
Ní àsìkò yìí ni ó wá ìyá a rẹ̀ tì, tí a sì ta òun náà sí oko ẹrú ní ọ̀nà àìtọ́..
wikipedia
yo
Èkejì ni ìlàkàkà rẹ̀ láti tako òwò ẹrú ní àsìkò tí ọ̀pọ̀ ènìyàn ń máakò sẹ́yin..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ju gbogbo rẹ̀ lọ, ìgbé ayé gámà yàtọ̀ tààrà pẹ̀lú u bí ó ti jẹ́ agbẹnusọ fún ènìyàn dúdú àti ẹni tí ó gba ara rẹ̀ là fúnra ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó ṣe ni láàánú wí pé ọgbẹ́mi yìí kò fi bẹ́ẹ̀ sọ púpọ̀ nípa ìtàn ìgbésí ayé ara rẹ̀, lẹ́yìn díẹ̀ tí a mọ̀ láti ara ìwé kan tí ó kọ nípa ìtàn ìgbésí ayé e rẹ̀..
wikipedia
yo
A bi Gama ni ọjọ kejidinlọgbọn Oṣu Kẹfa ọdun 1830 (28/6/1830) ni Ilu São Salvador..
wikipedia
yo
Luiz Mahin, Ànàgó (Olómìnira) ni ìyá a rẹ̀ ṣùgbọ́n òyìnbó Potogí tí ó ní owó lọ́wọ́ ní bàbá rẹ̀..
wikipedia
yo
Tí a bá wo àyíká tí a ti bí gámà, a ò rí i wí pé ní tòótọ́ ni, tí àwọn ènìyàn bá pè é ní "Aya kọ́kọ́ ní ti ìnàkí", "kìí -kìí-kìí-kìí”, "onirobinujẹ ọkàn" àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Ṣùgbòn rúi Braàjẹ́ pé ẹ ní "ẹni tí kìí ṣe ojo rárá"
wikipedia
yo
Tí a bá sì fẹ́ẹ́ mọ ohun tí ó bí àwọn àpèjẹ yìí, a gbọ́dọ̀ kọ́ ibi ara sí gbogbo ohun tí ó dìrọ̀ mọ́ ibi rẹ̀ àti ìdàgbàsókè rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní àkọ́kọ́, a bi gámà ní àsìkò tí àwọn àyípadà kan bẹ̀rẹ̀ sí í dé sí Brazil lẹ́yìn tí Brazil yọ kúrò ní oko Ẹrú (1840-1889)..
wikipedia
yo
Àwọn àyípadà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní dé bá ilẹ̀ Europe fúnra rẹ̀ ń ṣe Àkóbá fún Brazil ní àsìkò yìí..
wikipedia
yo
Ní àfikún, ní àárín àwọn aláwọ̀ dúdú, àsìkò yìí ni Dukùú ń wáyé láti ọ̀dọ̀ àwọn dúdú lórí ìlòdì sí òwò ẹrú..
wikipedia
yo
Àsìkò yìí gan-an tí gbọ́nmi-sii, omi-ò-too ń wáyé ní ìlú rẹ̀, Bahia lórí ọ̀rọ̀ òwò ẹrú yìí ní pàtàkì..
wikipedia
yo
Ibi gámà sì papọ̀ mọ́ rògbòdìyàn tí àwọn ọmọkùnrin gbé dìde ní ọdún 1835, ọmọ ọdún márùn-ún péré ni gámà ní àsìkò yìí..
wikipedia
yo
Okan ninu awon ohun ti o se okunfa iru igbe aye ti gámà gbe ni rògbòdìyàn ilu re ti a da pe ni incon Fidecia da Bahia (rògbòdìyàn ilu Bahia) eleyii ti o ti bere bii ogbon odun ki a to bi gámà..
wikipedia
yo
èyí sì mú àwọn ènìyàn ìlú Brazil ní ẹ̀mí ní ìgbà náà..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ sì ni a ríi kà wí pé àwọn ènìyàn pàtàkì orílẹ̀ èdè Brazil kan ti gba ẹ̀kọ́ ní orílẹ̀ èdè Europe níbi tí ìrọ̀rí àwọn ènìyàn ti kún fún Igbóminrira..
wikipedia
yo
Èyí sì ni àwọn ènìyàn mú bọ̀ wá sí ilẹ̀ ní àsìkò yìí..
wikipedia
yo
Àwọn nǹkan mìíràn tí ó dá ọ̀tẹ̀ sílẹ̀ ni bí àwọn olówó kò ṣe jẹ́ kí talaka ó ní ati bí àwọn ọmọ Brazil kò ṣe rí ààyè ninu ipò gíga ilé ìjọ́sìn..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ Brazil gan-an tún ń bá ara wọn jà ní àtàrí àwọ̀ dúdú àti àwọ̀ funfun..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ìgbà ni wọ́n sì máa ń dẹ́yẹ sí dúdú níbí àti dé ipò gíga, èyí sì ń bi Dukùú àti ọ̀tẹ̀ ní àsìkò yìí..
wikipedia
yo
Òmíràn nínú ohun tí a fi sàmì ìgbé ayé Gama ní rògbòdìyàn 1835, ohun tí ó bí ọ̀tẹ̀ yìí ni bí àwọn aláwọ̀ dúdú tí ó jẹ́ ẹlẹ́sìn Islam kan ṣe kó ara wọn jọ láti gba ìjọba lọ́wọ́ àwọn ìjọba ilẹ̀ Brazil..
wikipedia
yo
ÌJỌBA ILẸ̀ BRAZIL NÁÀ ṢÌ GBÉ OJÚ Àgàn SÍ ÀWỌN ÈÈYÀN YÌÍ TÀÀRÀ..
wikipedia
yo
Látàrí rògbòdìyàn yìí, ìjọba ilẹ̀ Brazil fi ohun ṣe ọ̀kan láti wá ìní kan ní ilé Afírika tí wọn yóò kó àwọn aláwọ̀ dúdú àárín wọn lọ nítorí pé wọ́n ń da àlàáfíà ìlú rú..
wikipedia
yo
Ẹni tí wọ́n bá sì gbá mú ní àtàrí rògbòdìyàn yìí, pípa ni wọ́n ń pa wọ́n tàbí kí wọ́n fún wọn ní ẹgba lọpọlọpọ, wọn a sì tún máa tì wọ́n mọ́ túùsíbẹ̀..
wikipedia
yo
Ó sì ṣòro fún ọmọ tí kò tíì pé ọdún mẹ́fà ní àsìkò yìí láti gbé ojú kúrò ní ìyá àjẹkùakátá yìí..
wikipedia
yo
Rògbòdìyàn yìí sì fa ikú fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ aláwọ̀ dúdú nípa kíkí òkun bọ̀ wọ́n lọ́rùn..
wikipedia
yo
Wọ́n fi ìyà jẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ nítorí pé wọ́n jẹ́ ọ̀rẹ́ àwọn Ànàgó lásán, wọ́n sì yin àwọn mìíràn ní ìbọn pa..
wikipedia
yo
Kì í ṣe ẹgba tí wọ́n ń fún àwọn eniyan gan-an ni ó ṣe àkóbá fún Luiz gámà ní ìgbà èwe, ṣùgbọ́n bí iye Ẹ̀gbá náà ṣe pọ̀ tó ní ojúmọ́ kan..
wikipedia
yo
Nítorí wí pé wọn a máa na ẹlòmíràn ní ẹgba bíi aadọta lojumọ; àwọn eniyan tí wọ́n sì dájọ́ ẹ̀gbà fún sì pọ̀ gan-an..
wikipedia
yo
Àwọn ẹrú tí ó wà láàrin àwọn eniyan yìí ni wọ́n dá pada fún olówó wọn lẹ́yìn ìjìyà wọn..
wikipedia
yo
èyí tí kò bá sì lè ṣiṣẹ́ dáadáa ni àwọn olówó wọn tún tà padà fún ẹlòmíràn..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ mìíràn ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí ó níí ṣe pẹ̀lú bí gámà ṣe dàgbà ni ó ṣẹlẹ̀ ní ìgbà tí ó wà ní ọmọ ọdún méje..
wikipedia
yo
Àwọn kan kó ara wọn jọ, tí wọ́n ja ìjọba gbà tipátipá ṣugbọn kò pẹ́ tí ìjọba fi ṣẹgun wọn pẹlu ohun èlò ogun..
wikipedia
yo
Ìdí ni wí pé SaBin ni ó síwájú rògbòdìyàn yìí, ó sì ṣe é ṣe kí baba Gama kópa nínú rògbòdìyàn yìí..
wikipedia
yo
Ní ìṣojú tani ni ilẹ̀ jíjó, èèyàn pípa àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ ló ṣe ṣẹlẹ̀ ní àsìkò rògbòdìyàn yìí..
wikipedia
yo
Inú ń rògbòdìyàn yìí ni ó ti wá ìyá rẹ̀ tì, tí baba rẹ̀ náà sì báà run..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ṣe ìrìbọmi onigbagbọ fún Gama, kò fi ẹ̀sìn Islam ati igbagbọ aláwọ̀ dúdú ìyá a rẹ̀ ṣeré rárá..
wikipedia
yo
Ẹkẹta Jehovahí ninu ohun tí ó ṣe okùnfà irú ìgbé ayé tí Luiz gámà gbé ni títa tí baba rẹ̀ táa sí oko ẹrú..
wikipedia
yo
Kékeré ni ojú rẹ̀ sì ti là sí ìyànjẹ tí ìyá rẹ̀ máa ń takò nígbà ayé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣugbọn ó jẹ́ ẹni tí ìyá rẹ̀ fi ìfẹ́ hàn sí láti kékeré..
wikipedia
yo
tita lẹ́rú rẹ jẹ ki o ni ọpọlọpọ iriri ti o dìrọ̀ mọ́ òwò ẹrú..
wikipedia
yo
Ìdí ni wí pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni ó kọ̀ ọ́ sílẹ̀ nítorí pé ìlú Bahama ti rògbòdìyàn pọ̀ sí jùlọ láti tako òwò ẹrú ni gámà ti wá, èyí ni ó sì fàá tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn fi ń rà á ní àràtúntà..
wikipedia
yo
Ọ̀kan ninu àwọn tí ó rà á lẹ́rú ni Cardoso jẹ, ní tòótọ́ Cardoso fi ìyà jẹ ẹ́ ṣugbọn òun náà ni ó jẹ́ kí gámà ka ìwé..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1848, gámà gba iṣẹ́ ológun lẹ́yìn ìgbà tí ó ti sá kúrò ní ipò ẹrú, ó sì gba okùn méjì kí wọ́n tó le è dànù nítorí wí pé ó gbé ẹnu sí ọ̀gá rẹ̀ kan..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó kúrò nínú iṣẹ́ ológun, ó bá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ṣiṣẹ́ ṣùgbọ́n àtakò òwò ẹrú rẹ̀ ń jẹ́ kí wọn ó lé e dànù kí wọ́n sì kà á kún aláìgbọ́ràn àti alágídí ènìyàn.Ní ọdún 1864, òwò ẹrú bẹ̀rẹ̀ sí í wá sí òpin díẹ̀díẹ̀ látàrí owó tí àwọn ènìyàn àti ìjọba gbé láti mú kí òwò ẹrú wá sí òpin..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn àsìkò yìí, gámà bẹ̀rẹ̀ sí ní lọ́wọ́ sí títú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹrú sílẹ̀ ní Brazil, ó sì gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbésẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ yìí..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1871, òfin tí ó fi ọwọ́ sí ìtúsílẹ̀ ẹrú di gbígbà wọlé..
wikipedia
yo
Ní gbogbo ìgbà tí àwọn aláṣẹ bẹ̀rẹ̀ sí fi ara mọ́ pípa òwò ẹrú rẹ̀ díẹ̀díẹ̀, Luiz gámà kò fi ar àmọ́ èyí, ó ń jà fitafita wí pé kí òwò ẹrú parẹ́ kàkàkía ni..
wikipedia
yo
Ìdí ni wí pé ọ̀pọ̀ ìgbà ni àwọn aláṣẹ ń fi ojú òfin owó ẹrú gbọ́ ilẹ̀ pẹ̀lú ọgbọ́n àlùmọ̀kọ́rọ́yí..
wikipedia
yo
Luiz gámà tún mú ọ̀rọ̀ yìí lọ sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin níbi tí wọn kò ti fi ara mọ́ ìdáǹdè ẹ̀ṣẹ̀kẹ́ṣẹ̀ fún gbogbo ẹrú..
wikipedia
yo
Títí tí gámà fi kú ní 1882, àbá yìí kò tí ì di òfin..
wikipedia
yo
Kí ó tó kú, ó tún dara pọ̀ mọ́ ìwé ìròyìn kan tí ó ń ṣiṣẹ́ lákọlákọ láti tako òwò ẹrú, orúkọ ìwé ìròyìn yìí ní Radical Pauliuse ó sì ṣiṣẹ́ kíkan kíkan pẹ̀lú ìwé ìròyìn yìí láti rí i wí pé òwò ẹrú di ohun ìgbàgbé kíákíá..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹtà, Oṣù Karun-un ọdún 1888, tí ó jẹ́ ọdún kẹfà lẹ́yìn ikú Luiz ganzaga pínto da gámà ní Aba tí ó fagi lé owó ẹrú di òfin ní ilẹ̀ Brazil..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ìgbé ayé Gama gẹ́gẹ́ bí amòfin, ònkọ̀wé àti olóṣèlú fi hàn gbangba pé ẹni tí ó nífẹ̀ẹ́ sí òmìnira tẹrú-tọmọ ni..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni Frederick Douglass ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà pẹ̀lú Cugoana, Equiano, àti Antoine amọ̀ ṣe ní ilẹ̀ Europe..
wikipedia
yo
Gbogbo ìgbìyànjú àwọn wọ̀nyí ni ó mú àyípadà rere wáyé ní Sentùú òmìnira.Ìwé tí a yẹ̀wòsomesome notes on the life and time of an Afro-Brazilian àbòèrèòníst of Yorùbá Descent by a Davis, Amherst College...
wikipedia
yo
Nínú ìtàn àròsọ/àtẹnudẹ́nu ilẹ̀ Yorùbá Ọ̀rànmíyàn tàbí Ọranyàn jẹ ọba láti Ilé-Ifẹ̀ Bẹ́ẹ̀ ni ó tún jẹ́ ọmọ Odùduwà..
wikipedia
yo