cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ohun ni ìtàn àròsọ ẹnu yí sọ wípé ó dá ìlú Ọ̀yọ́ sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ọdún 2001 Nàìjíríàìṣẹ̀lẹ̀ _* 23 December - Bola Ilai2001..
wikipedia
yo
YemitanYoruba oral Literaturepoetryiläliteraturedípò Yemitan Ìjálá Aré Ode Ìtàn Ìlú Oyè àti Ìgbétììgbẹ̀tì Ìlú Oyè àti Ìgbétì Ojú-ìwé 39–41..
wikipedia
yo
Ìtàn bí nwọ́n ti ṣe dá ìlú méjẽjì yí sílẹ̀ ni a sọ nínú ìjálá yĩ..
wikipedia
yo
Ìlú oyè kantí ú tipẹ́ ṣùgbọ́n ìgbẹ́tì ṣì wà síbẹ̀-síbẹ̀..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi Mo ti sọ ni ibẹrẹ iwe yi, O jẹ aṣa awọn ode lati ma ki ara wọn bi Nown ba pejọ..
wikipedia
yo
Ìdí rẹ̀ tí Oníkòyí kìí fií jẹ́ òkétékókórayìí rẹ̀ tí Oníkòyí kì í fi í jẹ òkété 34..
wikipedia
yo
Ibòmíràn wà tí ọmọ ibẹ̀ kò gbọdọ̀ fi omi gbígbóná mọ́ ara bí obinrin bá bímọ, ati Bebe lọ.Àwọn ọmọ Ọlọ́fà ojú-ìwé 35-36..
wikipedia
yo
Ohun tí í má ṣẹlẹ̀ nip é olúkúlùkù nínú àwọn ọmọ rẹ̀ yíò bẹ̀rẹ̀sí du láti ní ìpín tí ó tọ́ sí ọn nínú ogún bàbá wọn, olúkúlùkù kò sì jẹ gbà kí nwọ́n fi ọbẹ̀ ẹ̀hìn jẹ ọn ní iṣu.Ọlọburò àti ẹ̀kún ojú-ìwé 37-38..
wikipedia
yo
O ti gbójúlé Ọ̀fà ati ogún rẹ̀.iwe ti a gbOladipo Yemitan (1988) Ìjálá are ode University Press Limited, Ibadan, ISBN0- 0-57-52...17–1...
wikipedia
yo
Ilu Offa jẹ ilu kan ni Ipinle Kwara ni apa iwọ-oorun ni orilẹ-ede NaijiriaOffa ni Adasile nipasẹ Olalaye Ọlọ́fà-gangan; ọmọ-alade Ade lati Oyo, ati iru-ọmọ taara ti oba Ọ̀rànmíyàn ni Ile-Ife, ni bi ọdun13..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀wó ni olú-ìlú ìbílẹ̀ ti èdè abínibí ti IBM ti àwọn ènìyàn ti ó nsọ èdè Yorùbá ti Kwara àti Ọ̀ṣun states..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ ní ìjọba agbègbè àwọn ẹ̀wọ̀n márùn-ún márùn-ún, èyí ni; essa, Ojomu, Balogun, Sawo ati Igbo-I..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ka ní ilẹ̀ Alakija obìnrin ni Mọ́remí, ẹnití ó gbàgbọ́ pé ọgbà àwọn ilé-Ifẹ̀ sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn tí ń wá gbógun jà wọ́n, lóòrèkóòrè tí ó já Ifẹ̀, ilẹ̀ Yorùbá.Ìwé Ììtọ́ka sí Oládì Yemitan (1988) ìjálá aré òde University Press Limited, Ìbàdàn, ISBN0- 0-9-52.17-ìpínlẹ̀ Kwara..
wikipedia
yo
Boris Nikolayekùn Yeltsin (; ) (1 February 1931 23 April 2007) ni ó jẹ́ ààrẹ àkọ́kọ́ ilẹ̀ Rọ́ṣíà.ìtọ́ka àwọn ará Rọ́ṣíà..
wikipedia
yo
Adebayo Adefaratì (February 14, 1931 – March 29 2007) jẹ́ olóṣèlú ará orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Òndó tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Adéfaratì kú ni òjọ̀kandínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 2007.Ìtọ́kasíàwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Ondo..
wikipedia
yo
Ryszard tíṣàSchinìdáláre jẹ́ ọmọ ilé Pólándi tí ó jẹ́ òwé àti onílọ́lọ́ kù ní ọjọ́ kejì oṣù kìíní ọdún 2007.17 Ryszard tíṣàSC Ryszard Tanzania Laura & tiziano tercolokasi ara nkolándi pọ̀
wikipedia
yo
Cristina Eliṣabet Fernandez de Kirchner (; Born 19 February 1953), Sometimes referred to by her initials Cf, je oloselu ati agbejoro ara Argentina ati Aare ile Argentina tele..
wikipedia
yo
Oun ni obinrin akọkọ ti won yoo dibo yan gege bi olori ijoba (President) ni ile Argentina..
wikipedia
yo
Owó ọkọ rẹ̀, President Nestor Kirchner ni ó ti gba ìjọba lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ti dìbò yàn án wọlé ní ilé náà..
wikipedia
yo
Ìbò náà wáyé ní oṣù kẹwàá ọdún 2007.ìtọ́ka àwọn ará Argentina..
wikipedia
yo
‘Memphis jẹ́ ìlú kan ní ìpínlẹ̀ Tennessee ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí àwọn ìlú ní Tennessee..
wikipedia
yo
Ijipti tabi orílẹ̀-èdè ọlọ́míìnira Arabu ilẹ̀ Ijipti jẹ́ orílẹ̀-èdè ní àríwá Afrika.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ó ṣòro lati sọ pàtó igbà ti a dá ilú Ìjẹ̀bú silẹ̀ nítorí pé àwọn àgbà ti a fi ọ̀rọ̀ wa lẹ́nu wò wọn kò mọ̀-ọ́n-kọ tàbi mọ̀-ọ́n-kà..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n wọ́n sọ wí pé “Ajé” ni orúkọ ẹni tí ó dá ìlú Ìjẹ̀bú sílẹ̀ ń jẹ́.Ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ Ìjẹ̀búAjébu àti olóde jẹ́ òde..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti sọ, níbi tí ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn ti ń dé igbó kiri ni wọ́n ti pàdé ara wọn nínú igbó..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kan, wọ́n dá ìmọ̀ràn láàrin ara wọn pé ó yẹ kí wọ́n dá ibìkan sílẹ̀ tí àwọn yóo fi ṣe ibùgbé lẹ́yìn tí wọ́n bá ṣe ọdẹ lọ..
wikipedia
yo
Wọ́n lọ bi ìfà léèrè, ìfà sì ṣe atọ́nà ajẹ́bu wí pé kí ó lọ tẹ̀dó sí ibì kan, èyí tí à n pè ní íbéèrè..
wikipedia
yo
Ọlọ́dẹ àti ààjà darapọ̀ wọn tẹ ibi tí a ń pè ní ìta ààjàa dó, èyí sì wà ní ìlú Ìjẹ̀bú-Òde títí di òní yìí.Ibojì Ajébu wà ní íbéèrè lẹ́bàá Ọjà Oyingbo lọ́nà èjìrin tí olóde sì wà ní ibi tí à ń pè ní “ìtún olóde” ní ìta àǹtèa títí di òní yìí..
wikipedia
yo
Àwọn méjì tí ó jẹ́ akíkanjú jùlọ ìyẹn Ajébu àti olóde ni a pa orúkọ wọn pọ̀ tí ó wá di “Ajé-olóde” èyí tí à ń pè ní Ìjẹ̀bú-Òde títí di òní olónì yìí.Èdè Ìjẹ̀bú ni àwọn ẹ̀yà yìí máa ń sọ..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ àwọn ìlú tí a lè rí ní ẹkùn Ìjẹ̀bú ni Ìjẹ̀bú-Òde, Muṣin, Ata-Ìjẹ̀bú, Ìmọ̀pe, Odò-sọkaná, Àgọ́-ìwòye, Ìjẹ̀bú-igbó, òru, àwa, ilapo, isonyin, Ìparí-nlá, Odòkalaba, Idòwa, Merigo, lọ́runtàbí, Otansa ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Ìtàn sọ pé Ile-Ife ni wọ́n ti ṣì wá..
wikipedia
yo
Ọ̀kan nínú àwọn ìtàn wọ̀nyìí sọ pé óbàǹtà ni ó kó àwọn Ìjẹ̀bú kúrò ní Ilé-Ifẹ̀ wa tẹ̀dó sí Ìjẹ̀bú-Òde ìtàn mìíràn fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé orísun àwọn Ìjẹ̀bú ni wádáì..
wikipedia
yo
Ajébu àti ọlọ́dẹ tẹ̀lé olú-ìwà nínú ìrìnàjò wọn wá sí agbègbè Ìjẹ̀bú..
wikipedia
yo
Wọ́n sẹ́dàá orúkọ ìlú Ìjẹ̀bú-Òde láti ara àpapọ̀ orúkọ Ajébu àti Ọlọ́dẹ tí ó jẹ́ Àtètè tó gbajúgbajà.Adetoun gbà pé àwọn Ìjẹ̀bú tí wọ́n sì wá sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni a lè bá ní abẹ́ ọwọ́ mẹ́fà ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀..
wikipedia
yo
Ọwọ́ àkọ́kọ́ ni wọ́n wà lábẹ́ olú-ìwà tí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ Ajébu àti olóde tẹ̀lé àwọn wọ̀nyìí ni wọ́n tẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìletò dó ní ìlú Ìjẹ̀bú-Òde..
wikipedia
yo
Ọ̀wọ́ keji ni àwọn tô wà lábẹ́ arisu ìbátan olú-ìwà..
wikipedia
yo
Ọ̀gbọ̀rogòkó tí a mọ̀ sí ọbàǹtà tí ó ń wá olú-ìwà baba baba rẹ̀ tí ó ti kú kí ó tó dé ni ó jẹ́ ìpín kẹta.Ajálọ́run àti bálúfẹ́ ni ó jẹ́ adarí owó kẹrin..
wikipedia
yo
Òwò kẹfà ní ṣàánúolu àti elépèé àkọ́kọ́ tí wọ́n wá láti Ilé-Ifẹ̀ láti ṣe àwárí owó tí óbàǹtà..
wikipedia
yo
Àwọn wọ̀nyìí ni ojúlówó Ìjẹ̀bú-rẹ́mọ ní ìpìlẹ̀àwọn ìtọ́ka síYorùbá..
wikipedia
yo
ÌṢỌ̀KAN Afrika (gígé bi au ni ede geesi tabi ua jẹ́ ẹgbẹ́ ìkan tó ní àwọn orílẹ̀ orílẹ̀-èdè olominira kódà márùnléláàádọ́ta (55) bí ọmọ egbe.[Morocco]] ní orílẹ̀ orílẹ̀-èdè tí kìí ṣe ọmọ ẹgbẹ́ ẹkọ́ ìjò ìmọ̀ ..
wikipedia
yo
Òbàdàn tó wà lórí oyè lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí (ní 2016) ní Saliu AdetunjichaÌtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ yí wà ní ìwọ̀ Oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí olú ìlú rẹ̀ sì fìdí kalẹ̀ sí ìlú Ìbàdàn, tí olú ìlú rẹ̀ sì jẹ́ ìlú kẹta tí ó lérò púpọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì fìgbàkan jẹ́ ìlú kejì tó lérò púpọ̀ jùlọ ní Áfríkà rí..
wikipedia
yo
A da ipinle e Oyo sile ni ojo keta osu keji odun 1976..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ jẹ́ ìpínlẹ̀ kaàrún tí èrò pọ̀ jùlọ sí ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Púpọ̀ nínú àwọn ará ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ jẹ́ Yorùbá, tí èdè Yorùbá sì jẹ́ èdè tí wọ́n ń sọ jùlọ ní ìpínlẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Seyi Makinde je gomina ipinle Oyo.Àwọn agbègbè ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo ni agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìbílẹ̀ mẹ́tàlélọ́gbọ̀n..
wikipedia
yo
Hon.) Monsurat súnmọ́nu, first female speaker oyh and first female Senator from Oyo StateIbrahim Taiwo, General and Titábodè Thomas, politician and Lawyẹríkáá didọ̀mọ̀wé ìjọba ìpínlẹ̀ náà, Gómìnà tiwantiwa ni won ó yàn láti ke ke àti láti le ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ilẹ̀ Ọ̀yọ́..
wikipedia
yo
Olú ilẹ̀ ìpínlẹ̀ jẹ́ ìpínlè Ìbàdàn.Iṣẹ́ ọgbse oko tàbí iṣẹ́ ọ̀gbìn jẹ́ olú iṣẹ́ kan pàtó tí àwọn ará ilẹ̀ Ọ̀yọ́ máa ń ṣe..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà sìni, àwọn ìjọba ní oko ọ̀gbìn ní àwọn agbègbè bíi, ìsẹ̀yín, ìpapọ̀, ìlọ́ra, Ògbómọ̀sọ́, Èrúwà, ìrẹ́ṣàá, ìjàìyẹ́, àkúfọ́ àti làlùpọ́n..
wikipedia
yo
Àwọn oko ẹran ńláńlá tún wa ni Sadi, Fáṣọlá àti Ìbàdàn, ọkọ̀ Iwawàrà ní Milẹ̀ ní Ìbàdàn àti ètò ìdàgbàsókè ọ̀gbìn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí olú ilé iṣẹ́ ẹ wà ní ṣàwọ́n..
wikipedia
yo
Àìmọye ilé iṣẹ́ ọ̀gbìn tíbá jẹ́ tòkè ẹgbẹ́ àti tiwantiwa ni ó wà ní ìpínlẹ̀ náà.[23 Congu|date=December 2022}} ..
wikipedia
yo
Oruko re je yo latara itan Emirate ti Adamawa, pelu olu-ilu emiréètì tẹlẹri ti Léku ti o je gege bi olu-ilu ipinle Adamawa..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ náà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ oríṣiríṣi Àkóónú ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà pẹ̀lú àwọn ọwọ́ ẹ̀yà onílùú tí ó lé ní ọgọ́rùn-ún..
wikipedia
yo
Wọ́n dáa sílẹ̀ ní ọdún 1991 nígbàtí ìpínlẹ̀ gọngọlá tẹ́lẹ̀rí túká di ìpínlẹ̀ adáwà àti ìpínlẹ̀ Taraba.Láàárín àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ìpínlẹ̀ adáwà jẹ́ ìpínlẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ tí ó gbòòrò jùlọ ní ààyè tàbí agbègbè àti ṣùgbọ́n elésùnlédínlógún ní iye pẹ̀lú ènìyàn tí ó tó miliọ̀nnu mẹ́rìnlé-ní-ìdámẹ́rin gẹ́gẹ́ bí àbájáde ọdún 2016..
wikipedia
yo
Ohun tí a wá mọ̀ sí ìpínlẹ̀ adáwàwá ti ní olùgbé láti bí ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn kúnfún àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà pẹ̀lú bilẹ̀ (BchaMA), Bálì, Atàtà (gbWata), gùdù, Mbula-Bníléèwé, àti Nungu (Lunda (At) ní àáríngbùngbùn agbègbè náà; Kamwe sí àríwá àti ààringbùngbùn agbègbè náà; jíbùsí gúúsù tí o nasẹ̀; Kildi, Marga, Waga, ati wula ní ila-oorun, àti Muye ní gúúsù nígbàtí àwọn lànínn gbé jákèjádò ìpínlẹ̀ náà lemọ́lemọ́ gẹ́gẹ́ bí darandaran..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom jẹ́ Ìpínlẹ̀ kan ní agbègbè Eku-Ìjọba gúúsù-gúúsù orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó pín ààlà ní ìlà-oòrùn pẹ̀lú ìpínlẹ̀ Cross River State, ní ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ Rivers àti Ìpínlẹ̀ Ábíá, àti ní gúúsù pẹ̀lú òkun Atlantic..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ náà mú orúkọ rẹ̀ látara orúkọ ọ̀dọ́ lojúkìn ìbòẹ́ tí ó pín ìpínlẹ̀ náà sí ọgbọọgba kí ó tó sàn wọ inú Bight ti bo·me..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom yapa wa látara ìpínlẹ̀ Cross River nínú ọdún 1987 pẹ̀lú Olú-ìlú rẹ̀ Uyo pẹ̀lú àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ mọkanlelọgbọn.Láàárín àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom jẹ́ Ìpínlẹ̀ ọgbọ̀n tí ó gbòòrò jùlọ ní ààyè tàbí agbègbè àti Ẹlẹ́kẹtàdínlógún ní iye pẹ̀lú ènìyàn tí ó tó nírénununu marun-un-Abo gẹ́gẹ́ bí ìfojujú ọdún 2016..
wikipedia
yo
Àyè òde-oní ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ti ní olùgbé láti bí ọgọ́rùn-ún ọdún sẹ́yìn tí ó kúnfún àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà tí wọ́n jẹ́ Abatan Ibibio, Anaang, àti Obolo - òròn àwọn ènìyàn ní àríwá-ìlà-oòrùn, àríwá-ìwọ̀-oòrùn, àti agbègbè gúúsù ìpínlẹ̀ náà, lẹsẹsẹ..
wikipedia
yo
Ní àkókò ìmúnisìn, ohun tí a wá mọ̀ gẹ́gẹ́ bí ìpínlẹ̀ Akwa Ibom báyìí pín sí oríṣiríṣi ìlú-ìpínlẹ̀ bíi Ibom Kingdom àti Akwa Akpa kí ó tó padà di ìpínlẹ̀ lẹbẹ abo ìjọba Aláwọ̀-funfun ní 1884 gẹ́gẹ́ bí apákan oil Rivers SOent.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Anambra jẹ́ ìpínlẹ̀ kan láàárín àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ní agbègbè gúúsù-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè náà..
wikipedia
yo
Wọ́n dá ìpínlẹ̀ náà lé ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, ọdún 1991..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Anambra sopọ ìpínlẹ̀ Delta si Iwọ-Oorun, Ipinle Imo si guusu, Ipinle Enugu si ila-oorun ti Ipinle kogi si ariwa.Gẹgẹ bi abajade eto-ikaniyan odun 2022 awon olugbe ti won to nipèon mẹsan-an ni won gbe ni ipinle naa..
wikipedia
yo
Oruko ipinle naa ni won ṣawari ni odun 1976 látara aaringbùngbùn ila-oorun ìpínlè naa, won fun ipinle naa lorukọ ni ibamu pelu Odò OMMM, Odò to n ṣàn jakejado ipinle naa..
wikipedia
yo
Olù-ìlú rẹ̀ ní Awka, ìlú tó ń gbọ́rọ̀ ní kíákíá tí èrò inú rẹ̀ ti le si láti ẹgbẹ̀rún-lọ́nà-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin si miliọ̀nnunu mẹ́fà láàárín ọdún 2006 sí 2020..
wikipedia
yo
Ilu Onitsha, ti o je ibudo ilu ninu itan lati igba ìmúnisìn awon alawo-funfun, si je ọ̀gangan isowo láàárín ipinle naa..oruko-ina rẹ ni "imọlẹ orile ede" "Light of the Nation", Ipinle Anambra je Ipinle ẹlẹ́ẹ̀kẹjọ ti o gbooro julọ ni aaye tabi agbegbe ni orile ede, bi o ti le je wi pe idiju-jiyan rẹ wa pẹlu Onitsha, agbegbe ti o tobi julọ ti o si po ni ero ninu igboro ti awon eeyan inu re to Milivnu mejo-abo ni won ti ṣawari gege bi abajade AFRITS, ti odun 2020 ti o mu Onitsha jẹ igboro-ilu elekeji ti o gbooro julọ ni orile ede Naijiria ni iye ati ẹlẹ́ẹ̀kẹta ni ile-Adulawo..
wikipedia
yo
Bákan náà gẹ́gẹ́ bí àbájáde àwọn Demograchanal ti ọdún 2019 ìgboro Onitsha ẹlẹ́ẹ̀kẹtadínláàdọ́ta ìgboro-ìlú tí ó tóbi jùlọ lágbàáyé pẹ̀lú ẹ̀rọ miliọ̀nnu mẹ́jọ Anambra jẹ́ ìpínlẹ̀ tí ó pọ̀ jùlọ, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé ẹlẹ́ẹ̀kejì ni kíkéré ní agbègbè ni..
wikipedia
yo
Agbegbe ti a mọ si Ipinle Anambra ti jẹ agbegbe ti o lajú okeretan lati bii ẹlẹ́ẹ̀kẹ́sàn ògòru-UNN AD, pẹlu ilu àbáláyé nri, ti olu-ilu re je Igbo-U35tẹ́lẹ̀rí ninu itan láàárín ìpínlẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ Anambra jẹ́ Awonígbó, pẹ̀lú èdè Ìgbò tí ó jẹ́ gégé bí èdè àjùmọ̀ lọ jákèjádò ìpínlẹ̀ náà.ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
O mu oruko re latara Ilu-onitan Bauchi, ti o duro gege bi olu-ilu re..
wikipedia
yo
Wọ́n da ìpínlẹ̀ náà sílẹ̀ ní ọdún 1976 nígbàtí ìpínlẹ̀ àríwá-ìlà-oòrùntẹ́lẹ̀rí fọ́..
wikipedia
yo
O pelu awon OJÚLÓWÓ agbegbe ti o kun Ipinle Gombe, ti o di ipinle ti o dayato ni odun 1996.Láàárín awon ipinle mẹrindinlogoji ti orile ede Naijiria, ipinle Bauchi je ipinle Ẹlẹ́ta-un ti o gbooro julo ni aaye tabi agbegbe ati ẹlẹ́ẹ̀keje ni iye pelu eniyan ti o to nives mefa-abo-ni-ẹgbẹrun-iwe-ọgbọ̀n gẹgẹ bi abajade bi abajade odun 2016..
wikipedia
yo
Ohun ti a wa mo si Ipinle Bauchi ti ni olugbe lati bi opo odun sẹ́yìn kunfun awon orisirisi owo ẹya, pelu BOdarapo, butàwa, ati Warji si aaringbùngbùn agbegbe; awon Fúlàní, Kanuri, ati karai-kara ni ariwa; awon Fúlàní ati Gerawa ninu ayika ilu Bauchi; awon Z", (ṣayawa) ni guusu; awon tangale ni guusu-ila-oorun; ati awon jarawa ni guusu-iwo-oorun the Southwest.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Wikipedia jẹ́ iṣẹ́ òwò ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn kakiriàyè lati ṣe ìwé ìmọ̀ tó jẹ́ ofè ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ èdè ní orí Internet tí Wikimedia Foundation ń ṣe onígbọ̀wọ́.Wikipedia a ma ran ènìyàn púpọ̀ lọ́wọ́ l'pọ̀. àwọn iṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Bàtata jẹ́ Ìpínlẹ̀ kan láàárín àwọn Ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ní agbègbè gúúsù-gúúsù ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n dá ìpínlẹ̀ Bàtata sílẹ̀ ní ọdún 1996 wọ́n sì dá ààyè rẹ̀ yọ kuro ninu Ìpínlẹ̀ Rivers, ní èyí tí ó mú jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìpínlẹ̀ titun ní orílẹ̀ èdè..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Bàta àti Ọ̀pọ̀lọpọ̀ agbègbè rè bọ́sí ibi ẹkùn-omi tí ó léwu jùlọ, tí ó ṣeéṣe kí ó máa ṣẹlẹ̀ lọ́dọọdún..
wikipedia
yo
O pin aala pẹlu Ipinle Rivers si ila-oorun ati Ipinle Delta si ila-oorun, pẹlu awon omi ti Atlantic Ocean ti o je gaba lori awon aala guusu re..
wikipedia
yo
Àwọn sí ekọ́nimor, Kolokuma/Ọ̀pọ̀kuma, yẹ̀nàgoa, Nembe, Ogbia, ṣàgbà, brass àti gúúsù-Ijaw..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ náà pín ààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ Rivers, ní èyí tí oh jé apákan tẹ́lẹ̀rí, àti Ìpínlẹ̀ Delta.Èdè Ijaw, ni ó gbòòrò jù ní sísọ ìpínlẹ̀ Bàtasà pẹ̀lú Ísókó àti Urhobo tí wọ́n sọ ní àwọn ìlú àbáláyé ní ìpínlẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìlú Àpapọ̀ fún àwọn ará Urhobo tí wọ́n wà ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ṣàgbàma..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìpínlẹ̀ tí ó kéré jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí àbájáde ètò-ìkànìyàn ọdún 2006, bákan náà ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbègbè tí ó kéré jù ní ààyè..
wikipedia
yo
Wíwà rẹ̀ ní agbègbè Niger Delta, ìpínlẹ̀ Bàta ni odò àti ọ̀gbun níbí tí òkun ti pàdé, pẹ̀lú oríṣiríṣi omi láàárín ìpínlẹ̀ náà ni èyí tí kò jẹ́ kí ìdàgbàsókè òpópónà tó ṣe gbòógì ó wáyé.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ipinle Benue je okan lara awon ipinle ni agbegbe ariwa aaringbùngbùn orile ede Naijiria pelu eniyan ti o to nivesnu mẹ́rìnlé-ni-idáku gege bi abajade odun 2006..
wikipedia
yo
Wọ́n dá ìpínlẹ̀ náà sílẹ̀ ní ọdún1976 láàárín àwọn ìpínlẹ̀ méje tí wọ́n dá lé nígbà náà..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ náà gba orúkọ rẹ̀ látara Odò Benue tí ó jẹ́ odò ẹlẹ́ẹ̀kejì tí ó gbòòrò jù ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ naà pín ààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ Nasarawásí àríwá; ìpínlẹ̀Taraba sí ila-oorun; ìpínlẹ̀ kogi sí ìwọ-oòrùn; ìpínlẹ̀ Enugu sí gúúsù-ìwọ̀-oòrùn; ìpínlẹ̀ Ebon àti ìpínlẹ̀ Cross-Rivers sí gúúsù; ó sì tún pín ààlà pẹ̀lú orílẹ̀ èdè Cameroon sí gúúsù-ìlà-oòrùn..
wikipedia
yo
O ní àwọn olùgbé tí àwọn tí o gbilẹ̀ jùlọ jẹ́ àwọn ará Tiv, Idoma àti ìṣgede..
wikipedia
yo
Àwọn ọ̀wọ́ ẹ̀yà yóò kú ní Benue nìwọ̀nyí ẹtulọ, igbó, JukúnPeoples abbl..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1991, àwọn agbègbè ní ìpínlẹ̀ Benue (pàápàá jùlọ àwọn agbègbè tí wọ́n ti ń ṣọ́ ìgalà), ní ìbárìn pẹ̀lú àwọn agbègbè ní ìpínlẹ̀ Kwara State, ni wọ́n dá yọ jáde láti di apá titun ní ìpínlẹ̀ kogi..
wikipedia
yo
Awon ara Igbo ni a le ri ni awon agbegbe aala awon agbegbe ijoba ibile bii obi, oju abbl.itọkasi..
wikipedia
yo
Ipinle Borno je ipinle kan ni agbegbe ariwa-ila-oorun orile ede Naijiria, ti o pin aala pelu Ipinle Yobe si ila-oorun, Ipinle Gombe si guusu-ila-oorun, ati ipinle adáwa si guusu nigba ti o awon aala ila-oorun re parapo di aala orile ede pelu orile ede Cameroon, aala Ariwa re parapo di aala orile ede pelu orile ede Niger, ati aala Ariwa-ila-oorun re parapo di aala orile ede pelu orile ede Chad, léyìí ti o mu je ipinle Naijiria kan ti o pin aala pelu pin aala pelu meta..
wikipedia
yo
Ó mú orúkọ rẹ̀ látara ìlú onítàn Emirate ti Borno, pẹ̀lú Emirate àtijọ́ ti olú-ìlú Maiduguri tí ó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Borno..
wikipedia
yo
Wọ́n dáa sílẹ̀ ní ọdún 1976 nígbàtí ìpínlẹ̀ àríwá-ìlà-oòrùn tẹ́lẹ̀rí fọ́..
wikipedia
yo
Ó pẹ̀lú agbègbè tí a mọ̀ sí ìpínlẹ̀ Yobe báyìí, tí ó di ìpínlẹ̀ tí ó dá yàtọ̀ ní ọdún 1991.Ìpínlẹ̀ Borno jẹ́ gbègbè ẹlẹ́ẹ̀kejì tí ó gbòòrò jùlọ láàárín àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìndínlógójì ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ohun nìkan ló wà lẹ́yìn Ìpínlé-ger..
wikipedia
yo
Pelu bi aaye rẹ se ri, ipinlẹ naa jẹ ipinlẹ ẹlẹ́ẹ̀kọkànlá ti o gbooro julọ ni aaye tabi agbegbe pẹlu eniyan ti o to Milionnu mẹfa-din-ni-diẹ gẹgẹ bi abajade odun2016.Ipinle Borno ni olugbe lati bi opo odun sẹ́yìn kunfun awon orisirisi ẹya pelu DGHIrin, GlaPẹ̀lúpẹ̀lù, gùdùf, Loku, Mafa, ati mandara ni aaringbùngbùn eku naa; awon ara Afade, Yeru (BURI), ati kanembu ni gbùnnugbùnnu ariwa-ila-oorun; awon ara wàjà ni gbùnnugbùnnu guusu; ati awon ara Kbakugbo, Kamwe, Kilba, Margi groups ati ba ni guusu nigbati awon ara kan ati sRoko n gbe ni aarin Ariwa ati aarin ati aarin naa. Oun to apa.
wikipedia
yo
Ipinle Abia () je ipinle kan ni agbegbe guusu-ila-oorun orile ede Naijiria, ti o pin aala si ariwa-oorun ati ariwa-ila-oorun pelu awon Ipinle, ati ẹbọnyí, Imo State-oorun ipinle-oorun, Ipinle-oorun Cross River-oorun ipinle-oorun, ipinle-oorun Akwa Ibom guusu-oorun ati orile-oorun, ati ipinle Rivers si guusu..
wikipedia
yo
Olù-ìlú rẹ̀ ní Umuahia ti agbègbè tí ó gbòòrò jùlọ tí ó sì lajú jẹ́ Aba.Ìpínlẹ̀ Ábíá jẹ́ ìpínlẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹ́lélọ́ọ̀ọ́dúnrún tí ó gbòòrò jùlọ ní ààyè tàbí agbègbè àti ẹlẹ́ẹ̀kẹtadínlọ́gbọ̀n ní iye pẹ̀lú ènìyàn tí ó tó nimiliọ́nnu mẹ́rìndínlọ́gọ́rùn-ún-lọ́nà-ìgbà— gẹ́gẹ́ bí àbájáde ọdún 2016..
wikipedia
yo
lóde-òní àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ ábìà láti bí ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn kúnfun àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà, ṣùgbọ́n àwọn igbó ni wọn gbilẹ̀ jù nínú àwọn olùgbé yíi.Ni ti ètò ọrọ̀-ajé, iṣẹ́ wiwa epo àti ohun àlúmọ́nì Gasi ni ó jẹ́ gbòòọ́ ní ìpínlẹ̀ Ámọ́ Ámọ́ pẹ̀lú Ọ̀dà, nípàtàkì Iṣu, Àgbàdo, Taro, Epo Pupa, àti pákí..
wikipedia
yo