cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
f.A., ekíní nínú àwọn odù wọ̀nyìí a máa jẹ ọ̀lékú.Àwọn Yorùbá ka àwọn Odù wọnyu sí Òòṣà pàtàkì jùlọ, àwọn ojú Odù..
wikipedia
yo
Ẹsẹ̀-ìgbá ọ̀wọ́nrin méjì(a)ikin níí fàgbài seleátárì ni ó joorun ó pagbin ìsàlẹ̀ọlọ́bọ̀nhùnhùnhùn ni fapá ara rẹ̀ dá gbẹ̀du.níní.Àṣà Yorùbá ifá a ti rí i ní ojú ewé 46 apá kíní ìwé yí irú ipò pàtàkì ti Òrìṣà-nlá tàbi Ọbàtálá kọ́ láàrin àwọn òrìṣà àti Irúnmalệ ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
A ti gbọ́ pẹ̀lú pé jákè-jádò gbogbo ilẹ̀ Yorùbá ni nwọ́n máa mbọ̀ ọ́, nítorípé òun ni àwọn àgbà àtijọ́ gbà nínú ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ wọn pé ó jẹ́ igbákejì Olódùmárè, tí ó sì nràn án lọ́wọ́ lati tún ènìà dá nípa fífún un ní ojú, imú, etí, àti gbogbo ẹ̀yà ara míràn tí ó yẹ kí ẹ̀dá ni kí ó fi lè di ènìà pípé..
wikipedia
yo
...Àwọn nǹkan pàtàkì tí ìfà máa n dá lé lórí ọ̀rọ̀ nípa orí,ẹsẹ̀ àti àyà ìwà ìtàn àwọn òrìṣà àwọn ajogún àti àwọn ẹlẹyẹ ẹbọ ire àti àkíyèsí nípa ẹ̀dáìwé fún kíkà j..
wikipedia
yo
Ọdúnjọ (1969), ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀ Yorùbá, _ fún àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga, apá kejì, Longmans of Nigeria, ojú-ìwé 78-87.
wikipedia
yo
A lijàdú (1895) Ifa Mimọ Alabate United Star Printers Ltd.
wikipedia
yo
Ògúnbọ̀wálé (1980) àwọn Irúnmalệ Ilẹ̀ Yorùbá Evans Brothers (Nigeria Publishers) Limited..
wikipedia
yo
Débọ̀ Aròyìn (2006) Akòjì àlàyé àti ìbéèrè lórí àwọn ojú ọdú ìrú elyon Publishers Ileṣa..
wikipedia
yo
Àwọn òrìṣà tí Yorùbá nsìn (1) Ògún (2) Oríkì ogun Onírè (3) sopọnno (4) Songo Olúkòso (1)Ògún tí ó jẹ́ aláàbò fún àwọn tí ó nṣe iṣẹ́ ogun jíjà, àwọn ọlọ́dẹ, àti àwọn alágbẹ̀dẹ ní ogun; irin iṣẹ́ rẹ̀ sìn í ohunkóhun tí a bá fi irin ṣe..
wikipedia
yo
Nítorínáà, gbogbo àwọn tí ó bá ńfi ohun tí a fi irin ṣe ṣiṣẹ́ wà lábẹ́ ààbò rẹ̀ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Fún àpẹẹrẹ, àwọn tí ó nfi àáké tàbí ayùn gé igi; àwọn gbẹ́nàgbẹ́nà àti àwọn tí ó nran aṣọ; àwọn tí ó ti kọlà àti àwọn tí ó nran awọ; àwọn tí ó nwá ọ̀kọ̀ ilẹ̀, àti àwọn tí ó ńlu irin; gbogbo àwọn wọ̀nyí gba ogun bíó aṣíwájú àti aláàbò wọn; nwọn a sì máa bẹ̀ pé kí ó máà jẹ́ kí nwọ́n rí ìpalára nínú iṣẹ́ wọn....J.f..
wikipedia
yo
Ọdúnjọ (1969), ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀ Yorùbá _ fún àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga, apá kejì, Long Mans of Nigeria, ojú-ìwé 88-94...
wikipedia
yo
Ọlágúnbu Oyinlọlá (ọjọ́ February 3, 1951) jẹ́ ọmọ ológun tó tifẹ̀yìntì àti olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ alámòójútó ológun fún ìpínlẹ̀ Èkó láti 1993 dé 1996..
wikipedia
yo
Ni igba oselu ẹẹkeji, won dibo yan bi gomina ipinle Osun lati 29 May, 2003 de 26 November 2010 nigbati ile-ejo fagile idiboyan re sipo fun igba keji gege bi gomina ninu idiboyan 2007.Ìtọ́kasí gomina ipinle Osun..
wikipedia
yo
Séríkí n Goomaséríkí ń Goomaọba mẹ́wàá ìgbà mẹ́wàá, ìgbà kan ò lólè ayé gbọ́ séríkí ń Gooma, sanmọni Gooma ìgbà tí lọ nlẹ̀ yìí ohun gbogbo ti yí padà ní wàràwàrà..
wikipedia
yo
Ẹjọ́ ìgbà ti wọ̀ kuọ́ níbi tàná, ìgbà tó dé láwa ń lo ẹbí wa kò rárá,ọ̀pọ̀ èèyàn tí ò bá fẹ́ bágbà yí ló lè máa jágbúrin èsì lọ́bẹ mo rántí lákòókò kan nílẹ̀ yí mo kúkú ti gbọ́njú, n ò tí ì bàlágà ni..
wikipedia
yo
Pabe lo, pebẹ BO ÁEL ni lati Eko titi de 'Rárá, ko si mọ́tò bẹẹ ni ko si bata lese boorun ti n pawọ ori, Suamikan fami ti f ti fayerere Ile pataki, ko funra to ta ni o ni i ni i kini ti lágbára to kan, Tina o tun n pa tẹ̀rù-tọmọ bo pe bo ya ojú ojo a ro ní oorun a si wọ̀ọ̀kùn, ààjìn Dokita.. B.. Ni oríko lá.. ti oun pe lo ni adugbo kan ni lati iwo ori ni ‘K ni lati agba Kami lati ẹka lati bata Mi ti lágbára si lati Ìbàdàn lati pa ti n ko si Nami kan ni ko si ni adugbo rere lati si i kan * ọdún ti lágbára ti o o si pa - kan ni pe agbe ti i kan ni ko kan, pe a si wọ̀ọ̀kùn ti oun - ] ko ya oju ohun ti ko si bata ti pa ti pa ori ni lati agbá rere ti lati at ori kan, ko ni lati ni lati ni ko ni ni adugbo ti maa ni mo si mo si lati pa ti lati lati lati ro si lati ko si dá ni ko ni ko si oun là ni sinu ti n pa ori ni adugbo kan * ti ni ori kan kan ni ko ni ko ni ó ni i ko ni ni se * to hu ni mo pa
wikipedia
yo
Òṣùpá jèrè, a-mọ-lawọ́ bí ọkinkin,kinkin nǹkan rìbìtì tó ń tànmọ́lẹ̀ lálẹ́.Tí gbogbo wa fi ń tànmọ́lẹ̀ lálẹ́..
wikipedia
yo
Tí gbogbo wa fi ń gbafẹ́ orí, ìgbà tóṣù bá sì dàràn-mọ́jú, ara kálukú a sì rọ̀ wọ̀ọ̀, a sì di wọ̀mù lórí ibùsùn..
wikipedia
yo
Bó ti wù kómọdé gbádùn eréwọlé tó.Bó bá paná, eré a sì ríransinsin,orí mi àpé mi iyán ori orí mi àpé, àyà mi àkọ́bí-bọ̀ nígbà tórí ń gbéni kín ẹlẹ́rò ń wò? Orí lèjà fi í làbù jà, orí lọkáṣà fi í ṣe rere lálẹ́ odò orí la fi í meran láwọ̀ tá a kì í fi í meyìí tó leégún orí lóbìnrin fi í yán ó nlé ayé, orí lóbìnrin fi í jókòó nílé ọkọ rẹ̀ kò tóó dọjá-ìtàn..
wikipedia
yo
Orí ló òb tó fi dádé owó, orí ló ṣejoyè tó fi tepá ìlẹ̀kẹ̀..
wikipedia
yo
...Bí mo bá lówóbí mo bá lówóonígbèsè mo ọbẹ́ẹ̀ ṣe owó ni ò sì lọ́wọ́ tálákà náà le jẹdò ẹran, O le jẹ ṣákì, fìdìí, jẹ ibi ìkẹ́ inú ẹran..
wikipedia
yo
Ẹni bá ń ṣe fújà láìlówó lọ́wọ́, ṣe ló fẹ́ gbéra rẹ sí kòtò èèyàn ò lọ́wọ́ lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Ó ní Pẹ̀tẹ̀pẹ́tẹ̀ lè jábọ́ bá a bá bẹ̀diah ọ̀rọ̀ wò, onítọ̀hún fẹ́ ṣú bàrà ni..
wikipedia
yo
‘N ò nígbà, n ò lawọ́’ẹni náà ò tí ì sọ nkan tí kò ní..
wikipedia
yo
********* ******************************************* ******************************************************), Ẹkún Elédùmarè el Publishers, ISBN978 978 jáde 17 2–20- 20–20... 20
wikipedia
yo
Fáwẹ́lì Yorùbáfáwẹ́lì ni ìró tí a pè tí kò sí ìdíwọ́ fún afẹ́fẹ́ tàbí èémí tí ó ń ti inú ẹ̀dọ̀ fóró bọ̀ wá sí ọ̀nà ẹnu..
wikipedia
yo
Oríṣi méjì ni fáwẹ́lì èdè Yorùbá, àwọn ìsọ̀rí méjì náà ni...fáwẹ́lì àìránmúpè àti fáwẹ́lì àrànmúpè....fóníìmùfóníìmù ni òṣùwọ̀n ìró tó mú ìyàtọ̀ wà láàrín ọ̀rọ̀ méjì..
wikipedia
yo
Nínú orí yìí, a ó ṣe àgbéyẹ̀wò fóníìmù fáwẹ́lì àti fóníìmù kọ́ńsónáǹtì..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ fóníìmù èdè Yorùbá (a)(b)Bíbọ̀ ka ko sọ sẹwo fẹ́...Yorùbá Èdè olóhùnàwọn ọ̀rọ̀ Yorùbá a máa dún bí orin nítorí pé èdè olóhùn ni èdè náà í ṣe..
wikipedia
yo
Àwọn ọ̀rọ̀ kan ni sípẹ́lì kan náà, ṣùgbọ́n ìtumọ̀ wọn yàtọ̀ nítorí ohun ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ tí wọ́n gbèrú..
wikipedia
yo
Ascent & Thrust books Lagos, ISBN978-324-02-4-4, ojú-ìwé 8-25.èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Afrika ni orile keji títóbijulo ati Toñi awon eniyan julo lagbaye leyin Asia..
wikipedia
yo
ní bí 30.2 ẹgbẹgbẹ̀rún km (11.7 million sq mi) lápapọ̀ mo àwọn erékùṣù tó súnmọ́, ilé rẹ̀ jẹ́ 6% àpapọ̀ gbogbo ojú ayé àti 20.4% gbogbo ilẹ̀ ayé..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú ẹgbẹ̃gbẹ̀rúnkejì kan ènìyàn (ni 2009, ẹ wo tábìlì) ní àwọn agbègbè 61, èyí jẹ́ bí 14.72% gbogbo iye ènìyàn àgbáyé..
wikipedia
yo
Ni ariwa rẹ ni Okun Mediìgbàlàòkú wa, si Ariwailaọrun rẹ ni ilaọdọ Suez ati Okun Pupa wà lẹgbẹ Sinai Peninsula, si Guusuilaọrun rẹ ni Okun India, ati si iwoorun rẹ ni Okun Atlantiki wa..
wikipedia
yo
Afrika ni orile-ede 54 Lapapọ mo Madagascar, opolopo Erekusu ati orile-ede olominira sarawi Arabu Toṣèlúaralu, to je omo egbe isokan Afrika botilẹjẹpe Morocco lodi si eyi.Afrika, àgàgà Gbọ̀ngàn apailaọrun Afrika, je gbigba lopolopo latọwọ awon awujọ onisayensi pe Ibe ni ibi ti awon eniyan ti bẹrẹ ati hominidae Clade (Great Aapes), gege bi o se han pelu Iriri awon hominids pipejulo pipe ati awon babańlá won, ati awon ti won wa leyin won ti won péjú bi odun lẹ́gbẹgbẹ̀rún meje seyin - Lapapọmo sahe Tchaden, Australopithecus africanus, a a..
wikipedia
yo
Ergaster - pẹ̀lú èyí tó pèJùlọ nínú wọn Homo sapiens (ènìyàn òdeòní) tí ó jẹ́ ràdèé ní Ethiopia tó jẹ́ ọdún bí 200,000 sẹ́yìn.Afrika bo ìbúgédé mọ́lẹ̀, ó sì ní oríṣiríṣi àwọn agbègbè àgbàsílẹ̀; ó jẹ́ orílẹ̀ kan ṣoṣo tó gùn láti agbègbè àparíúrí Alọ́wọ́ró dé apágúúsù aláwòrọ.Orísun Ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ AFRIRI ni orúkọ àwọn ènìyàn tí wọ́n gbé ní àríwá Áfríkà lẹ́ Carthage..
wikipedia
yo
Orúkọ àwọn wọ̀nyí jẹ́ sísọ mọ́ “Afa” tí àwọn finikì, tó túmọ̀sí “eruku”, ṣùgbọ́n èrò 1981 kan ti sọ pé ó wá láti ọ̀rọ̀ èdè berber Ifrí tàbí Ifran totúmọ̀sí “CAv", in Reference tó cave jasperive..
wikipedia
yo
Afrika tabi ifri tabi Airr ni orukọ banú ifran lati Algeria ati Tripoli (ẹya Berber ti YaFran).Labẹ ijọba awọn ara Romu, Carthage di oluilu igberiko Afrika, to tun je kikomọ apa ẹ̀bá Odò Dayaya Oni..
wikipedia
yo
"-ka" ("CA") to je ilemẹ̀yìn Afrika je awon ara Romu to tọ́kasí "orile-ede tabi ile"
wikipedia
yo
1.15) Sọ pé ó jẹ́ Sisoloru fún Eroko, ọmọkùnrin ọmọọmọ Abraham gẹ́gẹ́ bí Gen..
wikipedia
yo
Nípa èyí Afrika jẹ́ fún àwọn ará Egypti, "Ilẹ̀ ìbímọ."Tanani Àtijọ́ ní ìbẹ̀rẹ̀ ìgbà Mesoso.[ik, Afrika jẹ́ jípo mọ́ àwọn orílẹ̀ ayé yìókù gẹ́gẹ́ bi Pange..A..
wikipedia
yo
Afrika pin awon jọjọ kanna ti orilegbangba yi ti o je sísọ̀rí lowo awon theropods, prosáùropods ati Ornithischians akokolo nígbàtí igba tdáhùn wá sópin..
wikipedia
yo
Àwọn ìkúta òpin jẹ́ Wira kãkiri Africa, ṣùgbọ́n wọ́n wọ́pọ̀ ní gúúsù ju àríwá lọ..
wikipedia
yo
Ìlá tó ya igba Triassic Soto si Jurassic lo fàlàsi ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ìsẹ̀lẹ̀ iparun tó ní IP ni lagbaye, botilẹjẹpe Strata Afrika ìgbà yi ko ti jẹ́ gbígbéwo dáada.Awon ìpele ilẹ̀ igba ìbẹ̀rẹ̀ Jurassik pinkiri lona kanna bí ti ìsun late Triassic, with more common outCrops in the South and less Common Fossil Beds which are predominated by Tracks to the North..
wikipedia
yo
As the Jurassic proceeded, larger and more iconic groups of DiOsaurs like sauropods and ornithopods Ackuted in Africa..
wikipedia
yo
Middle Jurassic Strata are neither well represented nor well studied in Africa..
wikipedia
yo
Late Jurassic Strata are also poorly represented Apart from the wọ̀ncular Tendagúru sàndídá in Tanzania..
wikipedia
yo
The late Jurassic Life of Tendagúru is very similar to that found in Western North America's Morrison formation.Ọ̀rúndún 9k-18K Afrika ki o to di ibiAlamusìn o se e se ki o ní orisirisi orile-ede otooto to ju 10,000 lo ati asejọba to ni orisirisi ilana ati àgbájọ oloselu..
wikipedia
yo
Ninu awon wonyi ni Ìdìpọ̀ ebi kekere awon aṣọ́de bi awon San ni apaguusu Afrika; títóbi, awon àdìpọ̀ Adimule bi awon Ìdìpọ̀ ibatan ebi awon elédè Bantu ni àpaaparin ati apaguusu Afrika, awon àdìpọ̀ ibatan adimule gidigidi ni ibi iwo ori Afrika, awon Ilẹ̀ọba saquin títóbi, ati awon ilu-ijoba ati awon Ilẹ̀ọba aladáwà bi ti awon Yoruba ni iwoorun Afrika, ati awon ilu oja eti awon Swahili ni ilaọrun Afrika.Nigba fi di orundun 9 kede oko laarin orile oba oba Adeoba, ti awon orile akoko wa ninu won ninu won, ti Sanko kakiri- lati awon agbegbe-Wale lati oko apapo de ibi Sudan..
wikipedia
yo
Awon to lagbarajulo larin awon orilejọba wonyi ni Ghana, gao, ati kanem-Bornu Empire..
wikipedia
yo
Agbara Ghana dinku ni orundun 11K sugbon Ilẹ̀mírànaye Mali rọpo rẹ̀, èyí ló sì di ọ̀pọ̀ gbogbo Apaiwoorun Afrika mu ní orundun 13K..
wikipedia
yo
Bé síni ní àwọn agbègbè Igbo Etiodo ìwọ̀òrùn Áfríkà, àwọn Ilẹ̀ọba alómìnira jàdìde láìní ipá kankan látọ̀dọ̀ àríwá mùsùlùmí.ÌFẸ́, tó jẹ́ àkọ́kọ́ lãrín àwọn ìlú-jọba tàbí Ilẹ̀ọba Yorùbá, sẹ́dàsílẹ̀ ìjọba lábẹ́ Ọba, ntón únjẹ Oò..
wikipedia
yo
Ife je ibi pataki esin ati asa ni Afrika, ati fun asa ibile ere gbigbe..
wikipedia
yo
Irú ìfijúwe ìjọba Ilé-Ifẹ̀ jẹ́ gbígbamúlò ní Ọ̀yọ́, níbití àwọn Ọba, tí wọ́n únjẹ Aláàfin ti fìgbà kan jọba lórí ọ̀pọ̀ iye ìlúorílẹ̀ṣàjọba àti Ilẹ̀ọba Yorùbá míràn àti ti àwọn tí wọn kò jẹ́ Yorùbá, Ilẹ̀ọba Dahomey àwọn fọ́n jẹ́ ibi tí wọn kò sọ èdè Yorùbá lábẹ́ ìjọba Ọ̀yọ́.Àwọn Almọ́raffìdí, jẹ́ Ọbarandẹran Berie láti Sahara tí wọ́n fọ́n kiri Aríwaapaiwoorun Áfríkà àti Peninsula ìbẹ̀rian nígbà ọ̀rúndún 11k..
wikipedia
yo
Bánú Hilal ati banú ma'Qil jẹ akopọ àọnọn ẹya Arab Bedouin lati Aradepo Peninsula ti on Kolo si iwoorun lati Egypt larin orundun 11k ati 13K..
wikipedia
yo
Ìkórèò fa ìdàpọ̀ àwọn Árábù àti Berif, níbi tí àwọn ará ilé ti di Árábù, bẹ̀ sìni àṣà Árábù gba àpilẹ̀ṣe àṣà ìbílẹ̀ ibẹ̀, lábẹ́ ìṣọ̀kan Islam.Àwọn agbègbè àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n wà ní ìpele yí ni wọ́n wà lábẹ́ àtọ̀ scheme for Geographic Arírẹ́gíons ti Àjọ United Nations, àti dátà tí ó rọ̀ mọ́ ìtọ́ka sí fún àpilẹ̀kọ..
wikipedia
yo
Where they differ, protálákàs are clearly indicated.Ìtọ́kasí àwọn orílẹ̀..
wikipedia
yo
Ìjálá sísun nípa àkókòìjálá fún àkókò kan nípa ìgbésí ayé àwùjọ kan ni èyí ma ń sábà bá mú..
wikipedia
yo
Aṣjálà tún lè yí padà bí ó bá fẹ́ lòó fún àwùjọ mìíràn.Ìjálá tí Aṣjálà bá sùn má ń ṣàfihàn bí àwùjọ náà ṣe rí nípa ìrísí, ìhùwàsí àwọn ènìyàn ibẹ̀, àṣà, ìbáṣepọ̀ ètò ìṣèlú àti ètò ọ̀rọ̀ ajé àwùjọ náà.Ewì nípa ẹyẹ àti ẹranko ẹranko, ẹyẹ, igi àti àwọn nkan mìíràn wọ̀nyí ní ìpájúlà má ń mẹ́nu bà nínú ìjálá nígbà tí ó bá wà láàrín àwọn ọdẹ ẹgbẹ́ rẹ tí àwùjọ kọ sí ewì alohùnnínú lítíréṣọ̀ Yorùbá, oríṣiríṣi ewì alohùn ni ó wà tí ó yàtọ̀ sí ìjálá..
wikipedia
yo
Bí Yorùbá ṣe ni ìjálá, ni wọ́n ni ẹ̀gẹ́, ọfọ̀, Ásan, ìyèré, rárá, ẹ̀ṣà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọoríkì nínú ìjàlàákú ohun tí o máa ń jẹ akejáálá lógún ni ó wà ní orí yìí..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń fi ìjálá kí ènìyàn a kìí sìí sábàá mọ ẹni tí ó ṣẹ̀dá irú ìjálá bẹ́ẹ̀..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ, ìjálá tí ó jẹ mọ́ ọba Abiodun ni ó wà ní orí yìí..
wikipedia
yo
Lílé ké ìjálá náà dáadáa ní oríyìn fún ẹni tí ó ké ìjálá kìí ṣe ti pé bóyá ohun ni ó ṣẹ̀dá rẹ̀.In the Repertonic of a master ìjálá-artist, there is usually a preponrance of ìjálá Poems which are euloùn on lebal progenitors or groups of progenitors..
wikipedia
yo
The praise Poems are anonymous Classics which date back to the Halcyon days of the Yoruba Kingdom during the reign of King Abiodun (1770–1830)..
wikipedia
yo
In rendering these Classics, the ìjálá-Chanter takes credit for his ability to recall the texts accurately from Memory and for his ability to chant them in the special traditional style..
wikipedia
yo
The credit for the Composition of the texts belongs to anonymous authors of ByGone eras....Character Porits in ìjálá Poem kan tí akéwì mọ dáadáa ni ó ke ìjálá nípa rẹ̀ ní orí yìí..
wikipedia
yo
Lóòótọ́, akéwì yìí yìn ín dáadáa, síbẹ̀ ó sọ àwọn òkodoro kan tí ó korò nípa rẹ̀.The theme of many an ìjálá Poem is the chárater of a kálẹ̀ personage who is well known to the poet..
wikipedia
yo
The poet presents a character-Portrait of the personage as a verbal Salute to the personage himself and so the Portrait tends to be KẹtaDókítàd in favour of him, but ìjọ, some unpalatable truths about him may be mentioned in the Po....dr..
wikipedia
yo
Eṣú jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òrìṣà tí àwọn ìran Yorùbá ń bọ..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn òrìṣà tí Olódùmarè rán láti ìkọ́lé ọ̀run wá sí ayé..
wikipedia
yo
Eṣú ni a le pè ní ọlọ́pàá tàbí àgbọ́firọ́ àwọn òrìṣà yòókù tí Olodumare rán..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé orúkọ èṣù ti yàtọ̀ láti orílẹ̀-èdè kan sí òmíràn, ọ̀nà tí wọ́n ń gbà sin í kò yàtọ̀.Ìgbàgbọ́ àwọn orúkọ mìíràn tí wọ́n ń pe Èṣù ní ẹlẹ́jẹ̀lù, Olúlànà, Ọbasín, Yísinbu, Àjọọlọ, Ọba ọ̀dàrà, onílé oríta, Ẹlẹ́gbára ògo, olóògùn àjísà, láàlú ògiri oko, láàlú Bara ẹlẹ́jọ́, láàroye ẹbọra ti jẹ́ látọ́.Eṣú jẹ́ alágbára, òrìṣà tó wúlò, bẹ́ẹ̀ sì ni ó jẹ́ òrìṣà tó wà ní ibi gbogbo tó bẹ́ẹ̀ tó jẹ́ pé nínú ọjọ́ mẹ́rin ti Yorùbá ni, gbogbo rẹ̀ ni wọ́n fi ń bọ èṣù..
wikipedia
yo
Èyí yàtọ̀ sí àwọn òrìṣà mìíràn tó jẹ́ pé wọ́n máa ń ní ọjọ́ kan nínú ọ̀sẹ̀láti fi bọ wọ́n, ọjọ́ gbogbo ni ti èṣù ọ̀dàrà”.Wọ́n máa kí èṣù báyìí a-bá-ní-wá-ọ̀ràn-bá-ó-rí-dá "'onílé- oríta"' "'L' "'O-kiri-ọkọ"' Àwọn oríkì tàbí orúkọ yìí fihan irú ẹni tí èṣù jẹ́..
wikipedia
yo
Òun ni ó ń kọ́ àwọn eniyan láti máa pe ojú meji ní gbogbo ọrọ̀ máa ń ní..
wikipedia
yo
Ó máa ń sọ́tùn, sósì má ba ibìkan jẹ́, bẹ́ẹ̀ náà ni ó máa ń tọ́ni sọ́nà..
wikipedia
yo
Ìdí nì yìí tí wọ́n fi sọ pé Èṣù ṣe pàtàkì láti ní ayé tó létò.gg bí ohun tí Olúwọ̀ Adéremi ìfàolèépín Adéremi láti Ọ̀yọ́ Aláàfin, sọ, ó ní Èṣù láàlú jẹ́ ẹ̀dá tó burú, tó kún fún ìkà, àrékérekè nígbà tí láàroye àjọngọlọ ọkùnrin ọdẹ jẹ́ ẹ̀dá tó dára, máa ń fẹ́ òtítọ́ àti ìwà ọmọlúàbí..
wikipedia
yo
Iranṣẹ Olodumare nìkan kọ́ ni èṣù jẹ́, óo máa ń jíṣẹ́ fún àwọn oriṣa mìíràn..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ gbádùn láàárín àwọn ajogún àti àwọn èèyàn..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni Eṣú ló wà nídìí gbígba ẹbọ àti pínpín ẹbọ fún àwọn ajogún.Àwọn ìtọ́kasí Yorùbáòrìṣà..
wikipedia
yo
Ọba Lajiwọ̀wọ̀ Ránṣẹ́ Atìoba Lajiwọ̀wọ̀ Ránṣẹ́ Gud Wọn Ní Ọjọ́ Tí A Ò Bá Dá Ní Kì Í Pẹ́..
wikipedia
yo
Bí ilẹ̀ ti ń mọ́, tó ń ṣú, bẹ́ẹ̀ ni ọjọ́ ń lọ geere bíi kẹ̀kẹ́ ológeere; bí òṣùpá ti ń ràn lálaalẹ́ bẹ́ẹ̀ ní ọjọ́ ń yọ geerege bí orí..
wikipedia
yo
...Oore nínú igbó ákílápáoore nínú igbó ákílápá ìlú ògiriìyandà jẹ́ ìlú kan tí a tẹ̀dó sí igbó Elujù ní ilẹ̀ ọ̀dàn..
wikipedia
yo
Agbára káká ni a fi ń ṣe alábàápàdé igbó jinringbọdọ̀..
wikipedia
yo
Ìdí rèé tí oore fi kúrò ní agbègbè ìlú rẹ̀, tó fi kọrí sí agbègbè ákílápá níbi tí igbó ńlá wà..
wikipedia
yo
Èrò ọkàn rẹ̀ ni pé, bí òun bá tilẹ̀ débẹ̀, bóyá òun á jẹ bá ohun tó jọ bí ọ̀sán pàdé..
wikipedia
yo
Jíjí di aya oorejíjí di aya oore ní ọjọ́ tó oore fẹ́ gbé ohun tí jíjí fẹ́ràn jù fún jíjí, gọngọ sọ lọ́jọ́ náà..
wikipedia
yo
Ní kùtù hàì ọjọ́ náà, láfẹ̀mọ́jú ni oníṣẹ́ ti kan ìdílé làṣọ̀rẹ́ lára pé ẹnìkan tún ti fi ìpinnu rẹ̀ hàn láti gbé jíjí níyàwó pẹ̀lú ohun tí jíjí fẹ́ràn jù..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ránṣẹ́ padà pé kí onítọ̀hún dá ara rẹ̀ lójú kí ó tó máa bọ̀, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, àwọn ó ní í jáde síta..
wikipedia
yo
Èyí táwọn ti fi àsìkò wọn ṣòfò lọ̀rọ̀ ọ̀rọ̀ jíjí tíé ó gẹ́ẹ́, alu-dùndún kì í dárin....jíjí àti àwọn òbí rèjijì àti àwọn òbí rẹ̀ ní ìlú Lápe-èdè, ọmọbìnrin kan wà tó ń jíjí..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n nítorí pé ó gbádùn láti máa kọ orin àlọ́-onítàn tó jẹ mọ́ ‘Jíjí’ tí í ṣe obìnrin inú àlọ́-onítàn yìí ni wọn ṣe ń pé ẹ ní jíjí..
wikipedia
yo
Orin náà ló báyìí jíjí àá gbọ́san, eku lòlògeere, ògiri lóko ọbẹ̀, ìrẹ́ lẹ́rù wọn, pinsìnsìnsìn TaWÒSÌ o, jíjí a gbọsán..
wikipedia
yo
…Jíjí àti ẹbí Láṣọ̀rẹ́ Ìyá lò lọ́mọ ní tòótọ́ gẹ́gẹ́ bí ohun tí àwọn Yorùbá máa ń sọ, Ìyá lalábàárò, Ìyá Jíjí tún tọ ọmọ rẹ̀ lọ pẹ̀lú òpẹlọpọ ẹ̀bẹ̀ àti àròyé ‘Jọ̀wọ́ ọmọ mi Àṣàkẹ́..
wikipedia
yo
Kín ló ti ṣe ọ̀ràn oko fífẹ̀ yìí sí? Gbogbo àwọn ará ìlú ló ń bú wa..
wikipedia
yo
Ṣe tí ìwọ náà bá ti mú ọkùnrin kan wá, irú ọ̀rọ̀ yìí ìbá má ti wáyé..
wikipedia
yo
Ilé ọkọ lobìnrin í gbé, ilé ọkọ ní Adépẹ̀kun obìnrin.'Jíjí pákó ọ̀rọ̀ sílẹ̀ Ọjọ́ tí a kò bá dá ni kì í pẹ́, kò pẹ́, kò jìnnà tí ọjọ́ ìpàdé ẹbí làṣọ̀rẹ́ fi kọ́ gẹ́gẹ́ bí ìpinnu wọn..
wikipedia
yo
Layọyọ to je olori won naa ti BO sori aga re..
wikipedia
yo
Gbogbo wọn ń tàkúrò sọ, wọ́n ń retí ọmọ wọn tí wọ́n pè sí ìpàdé..
wikipedia
yo