cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
A grammatical Analysis of mófoli Dialect of Yorùbá..
wikipedia
yo
A publication of the department of Gur-gon, Faculty of languages, University of education, windratta, Ghana..
wikipedia
yo
NeFẸ́RẸ̀Ẹ́ and the scope of NeFẸ́RẸ̀Ẹ́ in Yoruba mófoli..
wikipedia
yo
"On the formation of Questions in Èkégusìí and Yoruba mófoli." Papers in English and lingistics, Vol..
wikipedia
yo
Kéta ọ̀rọ̀-ìṣe nínú Yorùbá Ìjẹ̀ṣà (Mél'ary verbs in Ìjẹ̀ṣà dialect of Yoruba)..
wikipedia
yo
Readings in African dialelẹ́nulogy and Applied lingistics..
wikipedia
yo
Alkin by Felix AbiDemi Fẹ̀gàn & Akeem Segun Salawu..
wikipedia
yo
"Nemoke in Sixteen Yoruba dialects." Open Journal of Modern lingistics..
wikipedia
yo
Co-Àgbàó and published by the department of Ghanaian languages education (Gur), University of education, Windra, Ghana..
wikipedia
yo
Óas and published by the Department of lingistics and African languages, Obafemi Awolowo University, Ile-Ife..
wikipedia
yo
Alkin and to be published by the Department of lingistics and African languages, Obafemi Awolowo University, Ile-Ife..
wikipedia
yo
1 (in Press).Àwọn ìtọ́kasíàwọn ará Nàìjíríàèdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Janet ỌLÁÍDÉ Sheba ni Janet ỌLÁÍ Sheba jẹ́ ní Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Èdè àti Lítíréṣọ̀ Arika ní OAU, Ifẹ̀, Nigeria..
wikipedia
yo
Opolopo ise ni o ti se lori Litireso ile Arikarika.Àwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oyela jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ọ̀jọ̀gbọ́n ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ èdè àti Lítíréṣọ̀ Afirika ni ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, ní Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Láti ìgbà tí wọ́n ti dá Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí sílẹ̀ ní ọdún 1975 ó ti wà ní ibẹ̀..
wikipedia
yo
kí ó tó di àsìkò yĩ, ó ti n ṣiṣẹ́ ní Institute of African Studies, OAU, Ifẹ̀ láti ọdún 1970..
wikipedia
yo
Oun ni olukọ akọkọ ni ẹka-ẹkọ ede ati Litireso Afirika, OAU..
wikipedia
yo
O feyin ti lenu ise olukọni ni ọdun 1988.Awon itọka si awon ara Naijiria..
wikipedia
yo
Ọlábíyí Babalola Joseph yai (ọjọ́-ìbí 1939) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Benin àti ọ̀jọ̀gbọ́n Lítíréṣọ̀ ní Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Èdè àti Lítíréṣọ̀ Afíríkà ní Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ (Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University) ní Ìlú Ifẹ̀, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọdún 1988 ni olùkọ́ yìí fi ẹ̀yin ti ní Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí..
wikipedia
yo
yai tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi aṣojú orílẹ̀-èdè Benin sí UNESCO, bẹ́ẹ̀ sí ni ó tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi Alága Ìgbìmọ̀ apàṣẹ rẹ̀.Ìtọ́kasí Iyiyi..
wikipedia
yo
Karin Barberolu Litireso ni Karin Barber jẹ ni ẹka-ẹkọ ede ati Litireso Afirika fun ọjọ pipe..
wikipedia
yo
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí ni ó ti ń ṣiṣẹ́ nígbà tí ó ń kàwé oyè ọ̀mọ̀wé rẹ̀ lórí Lítíréṣọ̀..
wikipedia
yo
Wande Abimbola (Ọjọ́ìbí Oṣù Kẹfà 26, 1932 ní Ìlú Oyo, Nigeria) jẹ́ Olùkọ́ Lítíréṣọ̀ ní Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Èdè àti Lítíréṣọ̀ Arika ní Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ní Ilé-Ifẹ̀, Nigeria..
wikipedia
yo
O jẹ olori ẹka-ẹkọ yìí fun ọjọ pipẹ ki o to wa di 'Dean Faculty of Arts' ni ile-ẹkọ kan naa..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó fi ipò olórí ọkọ̀ yìí sílẹ̀ ni ó fẹ̀yìn tì..
wikipedia
yo
O se opolopo ise lori ede Yoruba ni pataki Ifa.ikeko rẹni odun 1963, Abimbola keko gboye itan ni University College, Ibadan.Ni odun 1971, o keko gboye Masters ni Northwestern University, Evanton, Illinois..
wikipedia
yo
O keko gboye doctorate nipa itan aroso lati University of Lagos ni odun 1966..
wikipedia
yo
Abimbola was the first PhD graduate of the University of Lagos..
wikipedia
yo
He became a full professor in 1976.Abimbola kọ àwọn akéèkó ní Fásitì mẹ́ta ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àwọn ná ní; University of Ibadan láàrín ọdún 1963 sí 1965, University of Lagos láàrín 1966 sí 1972, University of Ifẹ̀ láàrín ọdún 1972 sí 1991..
wikipedia
yo
O ti kọ́ ní àwọn Fásitì ní àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn bí Indiana University, Amherst College, Harvard University, Boston University, Colgate University, University of Louisville.Abimbola ti kọ àwọn ìwé lórí Ifá àti àṣà Yorùbá..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1977, Nok Publishers tẹ ìwé ti Abimbola kọ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Ifa Divination Poetry.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Segun Akeem Salawu je olukọ imo eda-ede ni ẹka-ẹkọ ede ati Litireso Afirika..
wikipedia
yo
Ó gba oyè ọ̀mọ̀wé ní ọdún 2006 lẹ́yìn tí ó kọ àpilẹ̀kọ lórí Yorùbá àti ọkọ ọ̀sányẹn..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ni ó ti ṣe lórí èdè Yorùbá.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
James bóde Agbaje jẹ olukọ ede ati Litireso ilẹ Afrika ni OAU, Ife, Nigeria..
wikipedia
yo
Lítíréṣọ̀ ni ó n kọ́ ni ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí ó sì ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ lórí Lítíréṣọ̀ èdè Yorùbá.àgbájé James bodè..
wikipedia
yo
[Abiodun Abọ́dúndé]]olùkọ́ Lítíréṣọ̀ ni Ọ̀jọ̀gbọ́n Abiodun Abọ́dúndé ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ èdè àti Lítíréṣọ̀ Áfíríkà ní Yunifásítì Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, ilé Ifẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ni ọ̀jọ̀gbọ́n yìí ṣe lórí àlọ́, kódà, púpọ̀ nínú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ dá le àlọ́ onítàn..
wikipedia
yo
Ó ṣiṣẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí kí ó tó fẹ̀yìntì..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn rẹ̀ ni ó ṣe aláìsí lẹ́yìn àìsàn ránpẹ́.Àwọn ará Nàìjíríààwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
láìdé Adewale (tàbí Uncle láìdé 1944 – 17 May, 2007) jẹ́ òṣèré orí ìtàgé àti olùko ọmọ ilẹ̀ Nàíjíríà, òṣìṣẹ́ ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ dírámà ní OAU, ilé-Ife kí ó tó ṣe lọ́lẹ̀ ní Ọjọ́ kẹtàkẹtàdínlógún, Oṣù karún-un ọdún 2007 (17/ ìdá)..
wikipedia
yo
Ọdún 1974 ni ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí lẹ́yìn ìgbà tí ó ti fẹ̀yìn tì lẹ́nu iṣẹ́ ọlọ́pàá..
wikipedia
yo
Ọdún 2006 ni ó fẹ̀yìntì lẹ́nu iṣẹ́ ni Dramatic Arts dépt., OAU, Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Kí Ọlọrun tẹ́ ẹ sí afẹ́fẹ́ rere.Ìtọ́kasíàwọn ara Naijiribọ̀wọ̀ òṣèré..
wikipedia
yo
Adeola Aditacles falẹ̀ye (Ọjọ́ìbí October 10, 1968) jẹ́ olùkọ́ ní Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ ìmọ̀-èdè àti Lítíréṣọ̀ Áfríkà ní Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University..
wikipedia
yo
Lítíréṣọ̀ apohùn ni ó ní ìfẹ́ sí jù lọ, ibẹ̀ sì ni púpọ̀ nínú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ dá lé lórí..
wikipedia
yo
Phillip Adédọ̀tun Ògúndèjì jẹ́ olùkọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ó jẹ́ olùkọ́ Lítíréṣọ̀ èdè Yorùbá ní Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Ẹ̀dá-èdè Áfíríkà ní ilé-ẹ̀kọ́ UI Ìbàdàn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
púpọ̀ nínú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ló dá lé orí eré orí ìtàgé ..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó ti gba oyè ọ̀jọ̀gbọ́n ní Yunifásítì yí.Àwọn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Okankan Salami lékàn Salamiìdí odò la sinlú agunyan; ìdí ọlọ la sìnkú ìlògi; níbí a rilẹ̀ sí la sìnkú olè..
wikipedia
yo
Ìdí ìgbà la sìnkú asíngba; ìdí gi la sìnkú ìṣọ́nà, níbí a rílẹ̀ si la sìnkú olè idi ejò là sìnkú ìbaka; níbí a rílẹ̀ si là sìnkú olè.Nígbà tọ́mọlọ́lù Oníkòyí kú lọ́jọ́sí; ẹ lo inú yàrá, ẹ gbélé Ken ikòtò-ìkòjì; ẹ gbélé Ken ìkọ̀kọ̀ ìkós.m..
wikipedia
yo
Raji (2003), Igi n da Leakybo Publishers, Ibadan, oju-iwe 83–86...
wikipedia
yo
Ajiji Aderemi (15 November 1889 – 7 July 1980) Titus Martins Adesoji Aderemi Tadeni je oloselu to laamilamila ati olori ilu tii se Ooni Ilu Ile-Ife Láàárín ọdun 1930 si 1980..
wikipedia
yo
Bákan náà ló ṣe gómìnà apá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà láàárín ọdún 1960 sí 1962..
wikipedia
yo
Gbajúmọ̀ onílẹ̀ ọlọ́nà ní Adéjijì Adéremi tí ó sì ní ọpọlọpọ ìyàwó àti ọmọ..
wikipedia
yo
Ọ̀kan lára àwọn ọmọ rẹ̀ ni òṣìṣẹ́ ìjọba tíí ṣe tẹ́júmade Alakija..
wikipedia
yo
lásìkò sáà ìjọba ìmúnisìn, ọba Ọọ̀ni ní agbára látàrí ètò ajẹmọ́ ìmúnisìn ìṣèjọba lọ́nà ẹ̀bùrú, tí wọ́n sì sá à lámì gẹ́gẹ́ bíi ọba ààyè onípò pàtàkì láàárín àwọn olórí ìlú ìbílẹ̀ ní ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ètò ìṣèjọba lọ́nà ẹ̀bùrú wà fún ìtanijí ìbílẹ̀ àti àjùmọ̀sọ nípa àwọn ètò ajẹmọ́ ìmúnisìn tí ó ń ṣe àkóbá fún àwọn agbègbè..
wikipedia
yo
Àwọn Bìrìtì gùn lé àwọn ìhun ati ipele àgbékà ìbílẹ̀ ajẹmọ́ṣẹ́lu tí ó ti wà tẹ́lẹ̀, pàápàá fún àwọn olórí ìlù ìbílẹ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, fún àjùmọ̀sọ ajẹmọ́ṣẹ́lu àti gbígba owó orí..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó yá, Ọọ̀ni pẹ̀lú àṣẹ àwọn olórí olóṣèlú aṣáájú ilẹ̀ Yorùbá fi ipò rẹ̀ dí àlàfo ìrẹ́jẹ tí ìyapa onípìn-ín láàárín àwọn Yorùbá ó sì gbìyànjú láti mú ìdàgbàsókè bá Yorùbá fún èròńgbà kan náà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1962, ọba náà gẹ́gẹ́ bí gómìnà wòáàdìmi lo agbára rẹ̀ láti yọ olórí agbègbè náà, nígbà tí ó keefin pé kò ní àtìlẹhìn ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ náà padà finá sí orogún Ajémólù ní agbègbè náà.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé ayé rẹ̀ ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù Belu, ọdún 1988 lásìkò rògbòdìyàn ogun abẹ́lé ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ọmọba Osundèyí Gbadebo ti idile ọlọ́ba ti Ile Ife ati arabinrin Adekunbi Tidara ti Ipetumodu (ti o je iyawo kekere ti o kere ju lọ) ni awon obi re..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ tí kò sí nílé, tí ó wà lójú ogun, ni wọ́n ṣe sọ ọ́ ní Adéremi Adésoji..
wikipedia
yo
Nígbà tí ọmọba Gbadebo darí dé, wọn ní láti fa ibiyẹmí tíí ṣe ẹ̀gbọ́nbìnrin Adéjijì tí kò lè pa ayò náà mọ́ra sẹ́yìn kí ó má baà lùgbàdì oògùn tìyébọ́ ara bàbá rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìgbà ti bọ́ gbogbo aṣọ oògun Asaabo tí ó sì ṣe ètù sí àwọn irúnmọlẹ̀ nígbà náà ni ó tó lé ìkàn àwọn ẹbí rẹ̀ Láì sí ẹ̀wù..
wikipedia
yo
Ọmọba Gbádébọ̀ tí ó jẹ́ olùAwo gbé ọmọ tuntun lọ sí ìdí ìlà láti wo wọnTáyéta ìkòkò tíì ṣe Adérẹmi..
wikipedia
yo
Ifá sọ àsọtẹ́lẹ̀ pé Adéremi yóò dé adé àwọn baba ńlá rẹ̀ ti ìgbà rẹ̀ yóò sì gbalẹ̀ gbọkọ, yóò sì ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn àjèjì láti ọ̀nà jínjìn..
wikipedia
yo
Ọmọba Gbadebo sọ fun iyawo rẹ̀ kí ó wá iyùn láti fi múra fun ọmọ náà torí pé èyí jẹmọ́ àmì ọba..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú ìgbàgbọ́ nínú Ifá, Adékunbi tii ṣe iyá rẹ̀ ń dáàbò bo ọmọ rẹ̀ nípa wíwẹ̀ ẹ́ nínú agbo títí tí ó fi dàgbà..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ kú ní 1897 nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́jọ..
wikipedia
yo
Torí pé bàbá rẹ̀ tètè kú, ìyá rẹ̀ ló tọ́ dàgbà.ìgbédìde ẹ̀sìn Kìrìsítíẹ́nì yí ìyá rẹ̀ lọ́kàn padà kúrò ní ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Ifá, torí náà ni wọ́n ṣe lọ forúkọsílẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Kìrìsítíẹ́nì ìbílẹ̀ tuntun ti St Phillips, ilé Ifẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àkọ́kọ́ tí yóò lọ sí ilẹ̀ilẹ̀ ìbílẹ̀ ní 1901.Ooni Ilé-Ifẹ̀ láti ọdún 1930 – 1980 ọmọba náà ní àfojúsùn..
wikipedia
yo
títako tí ó tako láti lọ ṣiṣẹ́ àó pẹ̀lú ẹ̀gbọ́n rẹ̀ agbá Ọmọba Adeire ló sokunfa iforukọsilẹ rẹ̀ ní Ilẹ̀ilẹ̀ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Anglican ní Ayétòrò Ilẹ̀ Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Adéjùmọ̀ tí wọ́n mọ̀ sí baba Ayétòrò tí ó padà di àna rẹ̀..
wikipedia
yo
O fẹ́ràn iṣẹ́ amòfin, kò bá sì ti rin ìrìnàjò pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ rẹ̀ nígbà náà bashiru Augusto..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n kò rí bẹ́ẹ̀ torí pé òun àti àyànmọ́ ni ọrọ̀ Aṣọtí - adé Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú pé ó tètè pàdánù bàbá rẹ̀, ó mú ife ohun tí ó fẹ́ ṣe ní ọ̀kúnkúndùn, kí á dúpẹ́ lọ́wọ́ ìyá rẹ̀ Adékúnbi tí kò gbàgbé àsọtẹ́lẹ̀ Ifá.Ìrírí àti ọlá ọmọba Adéremi sọ ọ́ di ọmọ oyè láì sì kọnu-u-Kohọ̀ lèyí gorí ìtẹ́ ní Ilé Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn tí ọba Adémílú wàjà, ó di Olúdì tí ó peregedé láti gorí ìtẹ́. Kejì, oṣù Ọ̀wẹ, ó di Ọọ̀ni ilé - Ifẹ̀ kọkàndínláàdọ́ta..
wikipedia
yo
Ọ̀bá Adéremi tètè faramọ́lé, ní ọmọ ogójì ọdún, òun ni Ọba tí ó kéré jù nínú àwọn Ọba ilẹ̀ Yorùbá nígbà náà..
wikipedia
yo
Pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn àgbà ìbílẹ̀ Ifẹ̀(Ọbalúfe, Ọbajiọ, Ọballọ̀ràn, Wasin, Ọbalúayé, Akọgun, jagun, Ẹ̀jẹ̀sí) wọ́n dá ìgbìmọ̀ ajẹmọ́ṣàkóso sílẹ̀ tí ó yí ìlú àtijọ́ náà padà ní ọdún mẹ́wàá tó ń bọ̀..
wikipedia
yo
Ọba Adéremi ṣe agbátẹrù ètò ẹ̀kọ́ lásìkò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ọọ̀ni tí ó sì yorisi ìdásílẹ̀ kọ́lẹ́jì Odùduwà ní oṣù Seere 1932.Ọba Adéremi ló dá ṣe agbátẹrù bí wọ́n ṣe kọ́ ilẹ̀ilẹ̀ náà, ilẹ̀ilẹ̀ àwòṣe ni pẹ̀lú nígbà náà; ìgbàgbọ́ Ọba Adéremi ni pé ètò ẹ̀kọ́ ni ọ̀nà kan tí ó dájú láti ṣe ìsọ̀lọ́jọ̀ nǹkan ajẹmọ́-ìgbàlódé. Ìṣẹ̀lẹ̀ gbòógì tó rinlẹ̀ lásìkò rẹ̀ ni ìdásílẹ̀ Yunifásítì Ilé - Ifẹ̀, èyí tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ sọ àṣeyọrí náà mọ ipò ọba Adéremi ni ilé ìjọba..
wikipedia
yo
Ọba Adéremi jẹ́ alága ìgbìmọ̀ àwọn ọba láti ọdún 1966 – 1980.Alaafia jọba lásìkò tó wà lórí ìtẹ́, bẹ́ẹ̀ ni ọpọlọpọ ọ̀tún ẹ̀rọ tí ó ṣe atọ́nà ọlá fún ọpọlọpọ ọmọ ìlú, pàápàá àwọn tí wọ́n wà ní Ẹ̀ka Iṣẹ́ Àgbẹ̀, níbi tí ohun alára ti jẹ́ Olórí okoòwòoríkì Ẹ̀mọkà kú ojú òpó di..
wikipedia
yo
Ojo iba mẹni ọ̀wọ̀ ni, ìba ti Pónísangò, ìba ti Poloya.Olùyẹ! ìtọ́kasí ọba àti ìjòyè ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá gbàgbọ́ wi pé Olódùmarè ló rán Ifá wá lati òde ọ̀run lati wá fi ọgbọ́n rẹ tún ilé ayé ṣe..
wikipedia
yo
Ọgbọn, ìmọ̀, àti òye ti Olódùmarè fi fún Ifá ló fún Ifá ni ipó nla láàarín àwọn ibò ni ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ifá si jẹ́ ọ̀rọ̀ ẹnu Olódùmarè ti ó si fi rán òjíṣẹ́ rẹ̀ Ọ̀rúnmìlà baba Avmiregun..
wikipedia
yo
Ìgbàgbọ́ Yorùbá ni wípé ni ìgbà kan rí, Ifá gbé òde-ayé fún igbà pípẹ́ ki ó tó padà lọ si ọ̀run..
wikipedia
yo
Ni igba ti ifa fi wa ni ile ayé, o gbe Ile-Ife fun igba perete..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ní ìgbà tí Ọ̀rúnmìlà fi wà láyé yìí náà, a tún máa lọ sí òde ọ̀run lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan tí Olódùmarè bá pèé láti wá fi ọgbọ́n rẹ̀ bá òun tún òde-ọ̀run ṣe..
wikipedia
yo
Nitori náà gbáyérun ni ifa nse.Ìtàn sọ fún wa wípé ọmọ mẹ́jọ ni Ọ̀rúnmìlà bí nígbà tí ó wà láyé, nígbà tí ó di ọjọ́ kan tí Ọ̀rúnmìlà nṣe ọdún ni ọ̀kan nínú àwọn ọmọ yìí tii ṣe abikẹhin pátápátá bá ṣe àfojúdi sí Ọ̀rúnmìlà, ni Orunmila bá bínú fi àyé sílẹ̀ lọ sí òde ọ̀run..
wikipedia
yo
Awon babaláwo maa nṣábàá lo ọ̀pẹ̀lẹ̀ ti wón ba fẹ́ daFá fun ẹlòmíràn..
wikipedia
yo
Awon babaláwo a maa gbe apo jeyín ko ejika ti won ba n re ode Ifa.Ẹbọ ifa rírú ẹbọ rírú se pataki fun eni ti a ba da ifa fun..
wikipedia
yo
Tí ó bá bẽrè lọ́wọ́ ifá, wọ́n le sọ pé kí ó lọ rúbọ fún ogun, ẹbọ ifá jẹ́ ètùtù pàtàkì nítorí tí babaláwo báni kí ènìyàn ṣe nǹkan òní láti ṣe é, kí òun pàápàá olè bá a ní ìgboyà wípé atẹ́Ẹ̀-Ẹ́ṣà, nítorí èyí ni àwọn babaláwo fi máa ńwí fún ẹni tí a ní kí ó rúbọ pé kí ó wá oúnjẹ fún àwọn alágigbòò rẹ̀.Èṣù àti Ifá bí a bá wo ilé àwọn babaláwo, a ó rí i wí pé èrè Èṣù kìí wọ́n nibẹ̀..
wikipedia
yo
Igba gbogbo ni àwọn babaláwo máa gbé ẹbọó lọ sí ibẹ̀, nwọn a máa bu epo lè yangí náà lórí, a máa rìn sùn nígbà gbogbo.Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ẹsẹ ìfà tí ó jẹ mọ́ èṣù..
wikipedia
yo
Nígbà míràn ewé, èbí sì dá bí ẹni ti ńwọ̀ Ifa ní agbára..
wikipedia
yo
Nínú ẹsẹ̀ Ifá a lè ri ohun ti ó jọ báyín "...ni Ọ̀rúnmìlà bá ti asẹ́ èṣù bọnu”
wikipedia
yo
Ìtumọ̀ èyí ni wí pé bí ìfà bá fẹ́ẹ́ ṣe nǹkan líle tí ó rí bí idán, àṣẹ èṣù ló ní láti lọ..
wikipedia
yo
Bí eégún ilée bàbá ẹni bá fẹ́ẹ́ bínú sí ni, láti ọ̀dọ̀ Ifá ni a ó ti gbọ́ èyí Wàá fún Ifá ni ipò aṣojú fún gbogbo àwọn irúnmọlẹ̀ yoku..
wikipedia
yo
Bí kò bá sí ìfàlà, iyì àti ọlá tí àwọn Yorùbá ḿbù fún gbogbo àwọn òrìṣà ilée Yorùbá rọ, tí ó sì nwá óńjẹ sí wọn lẹ́nu.Gẹ́gẹ́ bí a ti sọ síwájú, àwọn ọmọ Ọ̀rúnmìlà ni Ọ̀rúnmìlà fún ní ikin ifá mẹ́rìndínlógún nígbà tí ó padà lọ sí ọ̀run ti lọ sí wá sílé ayé mọ́.Nígbà tí a bá ń sọ̀rọ̀ ikin, a kò ní ṣe aláìmẹ́nuba àwọn ojú ọdú mẹ́rẹ̀ẹ̀rindínlógún nítorí ikin mẹ́rìndínlógún náà ni à ń lò lónìí láti béèrè nǹkan lọ́wọ́ ifá..
wikipedia
yo