cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ìdí ni pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilú ilẹ̀ Yorùbá ni wọ́n gbà pé Ilé-Ifẹ̀ ni àwọn ti lọ, èyí kò sì jẹ́ kí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ilú Ilé-Ifẹ̀ ṣe àjòjì sí wọn.Oríṣìíríṣìí ìtàn ìwáṣẹ̀ ló wà tó jẹ mọ́ ìsẹ̀dá Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Ìtàn tí a kà nínú ìwé tí ó sì tún ṣe rẹ́gí pẹ̀lú èyí tí a gbà láti ẹnu àwọn abẹ́nà ìmọ̀ wa kò ju ìtàn méjì péré tí í ṣe ìtàn àtẹ̀wọ̀nró àti ìtàn Mẹ́kà..
wikipedia
yo
Ohun tí èyí túmọ̀ sí ni pé àwọn ìtàn méjì náà ni wọ́n gbajúmọ̀ jù lọ..
wikipedia
yo
Nínú ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn ìtàn wọ̀nyí, a rí abala tí ó fara pẹ́ òtítọ́, a sì rí èyí tí kò fi gbogbo ara jẹ́ òtítọ́.Nínú ìtàn àtẹ̀wọ̀nró ni a ti gbọ́ pé láti ìsálú ọ̀run ni Olódùmarè ti rán Odùduwà wá tẹ ilé ayé dó..
wikipedia
yo
Abẹ́silẹ̀ rojọ́ ibẹ̀rí.Olodumare fún Ọbàtálá ní adìyẹ ẹlẹ́sẹ̀ marun-un ati erùpẹ̀ pé kí ó lọ fi tẹ ilẹ̀ ayé dó..
wikipedia
yo
ẹmu tó mú yìí mú kí ó sùn lójú ọ̀nà, kò le è lọ mọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tí Olódùmarè retí rẹ̀ títí tí kò rí i, ó rán odù tó dá ìwà tí í ṣe Odùduwà..
wikipedia
yo
Òrìṣà àtẹ̀wọ̀nró ni Odùduwà nítorí pé ẹ̀wọ̀n ni ó fi rọ̀ wá sí ilẹ̀ ayé..
wikipedia
yo
Bíilọ́kàn bíilọ́kàn omi ọkọ̀ ó dá dídà lomi ọkọ̀ ò dá,omi ọkọ̀ kì í yí, a dia fún Oòduà àtẹ̀wọ̀nrọwọn ní bọ rúbọ lọ́dún yìí ni ó goróyè baba ẹ̀ bí ó bọlọ́dún yìí ni ó goróyè baba Eo?” yìí kan náà ní olófin Àdìmúlà, onílé(ẹni tí ó ní ilé)..
wikipedia
yo
A gbọ́ pé ibi tí Odùduwà ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ rọ̀ sí ni wọ́n ń pè ní Òkè Oọ̀rám lónìí..
wikipedia
yo
Níbẹ̀ ni Odùduwà ti rí omi tí ó tẹ́jú lọ, ó sọ adìyẹ yìí sí orí omi yìí, adìyẹ yìí sì bẹ̀rẹ̀ sí tan yanrìn náà títí..
wikipedia
yo
Ibi tí ó tan yanrìn náà dé ní òkun, ibi tí Odùduwà wá tẹ̀dó sí ní Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Ìdí òtítọ́ rẹ̀ ni pé èdè ìfẹ́ “Ilé ẹ fẹ̀” hàn ninu orúkọ tí wọ́n sọ ìlú náà tí í ṣe Ilé Ifẹ̀ tí ó di Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Bákan náà, èdè wọn hàn nínú orúkọ oyè ọba wọn “Ọọ̀ni”
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí ìfẹ́ ṣe máa ń pe ọmọ tuntun jòjòló ní Abu roboto..
wikipedia
yo
Èyí ni pé Ọmọ tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ bẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé tirẹ̀ lóde ayé.Ewé ọpọlọpọ àkọọ́lẹ̀ ló fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé Ilé-Ifẹ̀ ni ayé ti bẹ̀rẹ̀..
wikipedia
yo
In fact Ilé-Ifẹ̀ is fàled as the spot where god created man white and black and from whence they disọdúnn all over the earth .(Gbogbo ẹ̀yà Yoruba ló tọsẹ̀ orírun wọn sí Odùduwà, a tilẹ̀ gbọ́ ọ nínú ìtàn pé Ilé-Ifẹ̀ ni Ọlọ́run ti ṣẹ̀dá ènìyàn, yálà funfun tàbí dúdú tí wọ́n sì ti ibẹ̀ fọ́n káàkiri ilé ayé)..
wikipedia
yo
Àwọn ìbéèrè náà ni pé; Njẹ́ ó ṣeéṣe kí ènìyàn fi ẹ̀wọ̀n rọ́ wá sí ayé? Njẹ́ a lè da iyẹ̀pẹ̀ sí inú omi kí ó má lọ sí ìsàlẹ̀ odò, kí á má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ pé adìyẹ? Ǹjẹ́ ó tilẹ̀ ṣe é ṣe kí adìyẹ kan ṣoṣo tán ilẹ̀ dé gbogbo ayé? Ǹjẹ́ ìwọ̀nba iyẹ̀pẹ̀ díẹ̀ lè tó láti kárí gbogbo ayé? Níwọ̀n ìgbà tí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè yìí bá jẹ́ rárá, a jẹ́ pé ìtàn ìwáṣẹ̀ pẹ̀lú àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ merìírí tí a kàn ní láti gbà gbọ́ ni..
wikipedia
yo
Ó jìnà sí òtítọ́ púpọ̀.Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn onímọ̀ ni wọ́n sọ nípa ìtàn kejì tí í ṣe ìtàn Mẹ́kà pé láti ìlú Mẹ́kà ni Odùduwà ti wá tẹ̀dó sí Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ìlú Mẹ́kà, Odùduwà yapa sí ẹ̀sìn abínibí rẹ̀ tí í ṣe ẹ̀sìn Lámúrúdu bàbá rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìyapa yìí mú kí ìjà ńlá bẹ́ sílẹ̀ láàrin Odùduwà àti àwọn ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí..
wikipedia
yo
Búramọ́, ọmọ Odùduwà pàápàá lòdì sí Odùduwà bàbá rẹ̀ nítorí pé ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn ẹlẹ́sìn mùsùlùmí ní ṣe..
wikipedia
yo
Inú bí Odùduwà, ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n sun ọmọ rẹ̀ náà ní ààyè..
wikipedia
yo
Inú bí àwọn ẹlẹ́sìn mùsùlùmí yòókù, wọ́n gbógun ti Odùduwà..
wikipedia
yo
Odùduwà sá àsálà kúrò ní Mẹ́kà, ó sì tẹ̀dó sí Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Ìtàn náà tẹ̀ síwájú láti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé Ilé-Ifẹ̀ ni àwọn ọmọ Yorùbá yòókù ti lọ..
wikipedia
yo
Ìtàn yìí fẹ́ dojúrú díẹ̀ nítorí oríṣìíríṣìí ìtàn ni a ń gbọ́ nípa ìran Yorùbá..
wikipedia
yo
Àwọn kan sọ pé ọ̀kanbí nìkan ni ọmọ Odùduwà ti ọ̀kanbí sì wà bí àwọn ọmọ méje tí wọ́n jẹ́ ọba aládé káàkiri ibi tí a le tọpasẹ̀ àwọn Yorùbá dé lónìí..
wikipedia
yo
Àwọn mìíràn gbà pé àwọn méje wọ̀nyí kì í ṣe ọmọ-ọmọ Odùduwà, pé ọmọ Odùduwà gan-an ni wọn àti pé kì í ṣe ìyàwó kan ṣoṣo ni Odùduwà ní..
wikipedia
yo
The children set up ọbaship and chieftaincy institutions in the various parts of Yoruba land(lára àwọn ìyàwó Odùduwà ní àtibá, omitótó àti Olókun..
wikipedia
yo
Àwọn ọmọ náà sí gbé ìjọba àti ètò ìṣèlú kalẹ̀ káàkiri ilẹ̀ Yorùbá).Ìtàn tí ó gbà pé Odùduwà ni ó bí àwọn ọmọ méje tó tẹ ilẹ̀ Yorùbá dó sọ pé Olówu ni àkọ́bí Odùduwà..
wikipedia
yo
Olówu yìí ni ó gbé àkọ́bí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin wa kí Odùduwà..
wikipedia
yo
Ọmọ náà bẹ̀rẹ̀ sí í ké, ó sì ń fà mọ́ adé orí baba ìyá rẹ̀..
wikipedia
yo
Odùduwà sí adé, ó sì fi lé ọmọ náà lórí, ọmọ náà sì gbàgbé sùn lọ tòun Tádé lórí..
wikipedia
yo
Èyí mú kí Odùduwà yọ̀ǹda Adé fún ọmọ náà nígbà tí ó jí..
wikipedia
yo
Bóyá ìdí nìyí tí wọ́n fi máa ń kí àwọn Òwu ní Asunkún Gbadéde Ọmọ Arunmi Orunmi gbó Ọmọ Igbomin, àrìnkáté jí kùtù Kúrí ìgboro bójú àwọn ọmọ Odùduwà tó kú lẹ́yìn olówu ní Alákétu ti Ketu, Ọba Ìbìní, Ọ̀ràngún Ilé I, Oniwó ti ilẹ̀ Aláta, Olúpópó tí í ṣe Ọba Pópó àti Ọkàadé
wikipedia
yo
Ìtàn tó tọ́ka sí ọ̀kanbí gẹ́gẹ́ bí ọmọ kan ṣoṣo tí Odùduwà bí náà gbà pé Oranyàn ni àbígbẹ̀yìn ọkànbí..
wikipedia
yo
Ìjìyà kò sí nílé, àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ sì pín gbogbo dúkìá baba wọn mọ́ owó, ilẹ̀ nìkan ni wọ́n fún un..
wikipedia
yo
Ó gba ilẹ̀ tí wọ́n pín fún un, ó sì sọ ọ́ di dandan fún àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ láti máa san ìṣákọ́lẹ̀ lórí ilẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Èyí mú kí ó di olówó, alágbára ati olókìkí láàrin àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀..
wikipedia
yo
Lára àwọn ìlú náà ni Oyo-ilẹ̀, ahoro oko, Ikoyi, ilẹ̀ Èkó, ìrẹsa àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àwọn òpìtàn mìíràn ń fi Aláké ẹgba àti Obokun ti Ìjẹ̀ṣà mọ wọ́n..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá tó si wà ni orílẹ̀ èdè Benin pin si méjì ‘Idà' àti ‘Manioṣù
wikipedia
yo
Àwọn onímọ̀ bíi Abimbola, Turner àti Watkins ti ṣe àlàyé pé àwọn ẹni tí wọ́n kó lo orílẹ̀ èdè 'Cuba', 'Brazil' àti America', wà níbẹ̀ lónìí tí wọ́n ń gbé èdè àti àṣà Yorùbá lárugẹ..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá tó wà ní 'Cuba' ni wọ́n ń pè ní 'Lucumi]
wikipedia
yo
Àwọn tó wà ní ‘Brazil’ ni wọ́n ń pè ní ‘Go'.Gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ ṣáájú, abala kan ìtàn tí ó sọ pé Odùduwà wá láti Mẹ́kà fara pe òtítọ́ bẹ́ẹ̀ sì ni apá kan rẹ̀ jìnà sí òtítọ́..
wikipedia
yo
A lè ka ìtàn Mẹ́kà yìí sí òtítọ́ nítorí pé bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé oríṣìíríṣìí àkọọ́lẹ̀ ló wà tó tọ́ka sí Odùduwà àti Ilé-Ifẹ̀ gẹ́gẹ́ bí orírun ọmọ Yorùbá ti oríṣìíríṣìí àkọọ́lẹ̀ sì wà pẹ̀lú pé Mẹ́kà ni Odùduwà ti wá sí Ifẹ̀, ìtàn Mẹ́kà jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà ju ìtàn àtẹ̀wọ̀nró lọ tí a bá fojú ẹ̀kọ́ nípa ìtàn wò ó.Tí a bá fi ojú ìmọ̀ sáyẹ́ńsì àti ìmọ̀ ìbára-ẹni gbépọ̀ wo ìtàn Mẹ́kà yìí, a kò lè kà á sí òtítọ́ rárá..
wikipedia
yo
Charles Darwin jẹ́ Onímọ̀ Àdáyébá ọmọ Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì (Ọjọ́ Kejìlá oṣù Kejì ọdún 1809 – ọjọ́ ọ̀kọ̀kandínlógún oṣù kẹrin ọdún 1882) tí ó mú àbá àti òfin tí ó de ẹ̀ro ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ wípé gbogbo ohun ẹlẹ́mi pátá jọ wá láti ọ̀dọ̀ adẹ́dàá kan náà ni…Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1809àwọn Ọjọ́lọ́lọ́ ní 1882àwọn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì kúkurú..
wikipedia
yo
Émile Durkheim (April 15, 1858 – November 15, 1917) je onimo awujo omo ile Fránsì ti o ko ipa pataki ninu imo awujo ati imo eda..
wikipedia
yo
Ó kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé lórí ẹ̀kọ́, ìwà ọ̀daràn, ẹ̀sìn ìgbàẹ̀mí araẹni àti lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ka àwùjọ.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1858Àwọn Ọjọ́aláìsí ní 1917àwọn amòye ará Fránsì..
wikipedia
yo
Maximilian Carl Emil Weber (21 April 1864-14 June 1920) jẹ́ onímọ̀ ètò ìnáwólé àti onímọ̀ àwùjọ ọmọ ilé Jemani tí a mọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan nínú àwọn olùdásílẹ̀ ẹ̀kọ́ nípa àwùjọ àti iṣẹ́ìjọba ìgboro.ìtọ́kasí Weber Max..
wikipedia
yo
Jürgen habermas (Abi ni osu June ojo 18, odun 1929 ni ilu Düsseldorf) je amòye ati onimo awujo omo ile Jemani ni ẹka imo oye to je mo agbeyewo ero ati asa Amerika lori oyegangan..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ láti inú iṣẹ́ rẹ̀ lórí ìko ìfijì tí ó gbé lóri ẹ̀rọ iṣẹ́ ìṣèsí àwọn ọjọ́ ní 1929àwọn amòye ará Jẹ́mánì..
wikipedia
yo
Fágúnwà kọ.Ọ̀rọ̀ ìipo ìtàn-àròsọ yìí wà fún tọmọdé tàgbà lọ́kùnrin lóbìnrin tí wọ́n mọ èdè Yorùbá kà dáadáa..
wikipedia
yo
Oun pelu awon Ìyòókù re bíi ògbójú ọde ninu Igbo Irúnmọ́lẹ̀, Ìrèké Onibùdó, Irindodo ninu Igbo Elégbèje ati Igbo Olódùmarè, ti D.O Fágúnwà ko jé okan gboogi lara iwe ti awon omo ilẹ̀ilẹ̀ giga Yunifásítì tàbí ilẹ̀ilẹ̀ àwọn olùkọ́ni fún iṣẹ́ akadá lọ́pọ̀ ìgbà..
wikipedia
yo
Iṣẹ́ gbòòrò lórí ìwé bíi ìtúpalẹ̀, lámèyítọ́, abbl Bákan àwọn akẹ́kọ̀ọ́ le lo fún iṣẹ́ àpilẹ̀kọ fún àṣekágbá ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Fágúnwà (2005) Àdììtú Olódùmarè Ìbàdàn; Evans Brothers (Nigeria Publishers) Limited, ISBN978-126-126-7..7..
wikipedia
yo
Ogún nínú ìtàn àròsọ Ẹ̀sìnwà-dénú ni ilé Yorùbá jẹ́ òrìṣà tó ní agbára lórí iná, ìrìn, ìṣọdẹ, ìṣèlú àti ogun.”Ọmọ tí yóò j’Àsàyí, kékeré ló ti njẹnu ṣámúṣámú lọ.” Òwe àwọn àgbà yìí ló bá ẹni tí ó kó ìwé yìí mú ọ̀gbẹ́ni Olatubosun Ọládàpọ̀, nítorí àkókò tí ó ńkẹ́kọ̀ọ́ ní ilé-ìwé àwọn olùkọ́ ti lùkù Mímọ́ ni ó kọ ìwé yìí, nílùú Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Lákòókò yìí, mo ní àǹfàní àti jẹ́ olùkoọ rẹ̀ nínú ẹ̀ka ẹ̀kọ́ Yorùbá, àti láti tún jẹ́ alábojútó ẹgbẹ́ ìjìnlẹ̀ Yorùbá ti Kọ́lẹ́ẹ̀jì náà..
wikipedia
yo
Lọ́nà méjèèjì yìí ni ọ̀gbẹ́ni Ọládàpọ̀ ti fi ara rẹ̀ hàn bíi akọni nínú èdèe Yorùbá..
wikipedia
yo
Dé ibi pé ní ọdún kẹta rẹ̀ ní Kọ́lẹ́ẹ̀jì, òun ni a fi jẹ alága ẹgbẹ́ ìjìnlẹ̀ Yorùbá ti Kọ́lẹ́ẹ̀jì náà..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó sì Diká ẹ̀ kí á máa wá eré tí ẹ̀gbẹ́ yóó ṣe ní ọdún 1967, eré tirẹ̀ yìí ni a yàn pé ó gbayì jù nínú gbogbo àwọn eré tí a yẹ̀wò nígbà náà..
wikipedia
yo
Awon ti o wo ere naa nigba ti awon omo egbe se e ni gbongan sẹntinárì ni Ake, Abeokuta ati ni gbọngan Apejọ ti Ile-ẹkọ giga ti Ilu Ayétòrò ni, "KàAT -le awo-pada-sẹhin-sẹhin” ni ere naa i-se..
wikipedia
yo
Èyí ló fún mi ní ìdùnnú láti lè kó ọrọ̀ asọ̀siwaju yìí lórí ìwé ogún làkáàyẹ..
wikipedia
yo
Ó fi orísirísi àṣà Yorùbá hàn; ju gbogbo rẹ̀ lọ, ó kọ́ ènìyàn lọ́gbọ́n lóríṣiríṣi ọ̀nà.
wikipedia
yo
Osùnsùn Ọládàpọ̀ (1983) Ogun làkáàyẹ Ìbàdàn; Oníbọnòjé Press And Book Industries (FM) Ltd..
wikipedia
yo
Thomas Makanjuola ilésanmí Thomas Makanjuola ilésanmí (2002) Ewu àgbà Ìbàdàn; University Press PLC Ìbàdàn, ISBN978-030-8-23-7 ojú-ìwé 68.Òhun gún-un mọ̀ mo ń sọnu yìí..
wikipedia
yo
Ohun ràbàtà ń pòórá láwùjọ asùwàdà, ọmọ adáríhunrun ni kò náání àwọn ãfin Olokun wọlé tọ̀ wá wá..
wikipedia
yo
Wọ́n fara nù wà lára, wọ́n ṣe bí eré bí ẹrẹ̀, wọ́n jí orí olókùn lọ..
wikipedia
yo
Wọ́n po mini mini bí ológìnní, wọ́n gbé iṣẹ́-ọnà ìṣẹ̀ǹbáyé ló mọ gbogbo ọmọ Oòduà lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Àgọ́ eégún ń pòórá nígbó ìgbàlẹ̀, ilẹ̀ orí ọlọ́jọ́ gbọọrọ ti báfẹ́fẹ́ wọn lọ..
wikipedia
yo
ẹdan tó ní láárí ń bẹ ní Múṣì, ni ilé ààbò fún ìtọ́jú nǹkan ìṣẹ̀ǹbáyé, tí àwọn ẹni funfun tí wọ́n dira bí asínwín fi jí wa lóhun ribiribi lọ...
wikipedia
yo
Ọọ̀ni ti Ilé-Ifẹ̀ ni orúkọ ọba aládé Ilé-Ifẹ̀ àti olórí nípa tẹ̀mi fún gbogbo ìran Yorùbá..
wikipedia
yo
Ipò Oòni ti wà ṣáájú ìjọba Odùduwà, èyí tí àwọn onímọ̀ sọ pé ó ti wà láti bíi Sétúrì keje sí kẹsàn-án.Lẹ́yìn Ìpapòdà Odùduwà àti ìpàdánù orí-oyè fún ogun, àwọn ọmọ lẹ́yìn Ofúùwa tán kárí Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Àmọ́ ìtàn mìíràn fi yé wa pé ogun ló mọ́ ọn mọ̀ rán àwọn ọmọ Odùduwà láti ṣe ìtànkalẹ̀ ìran Yorùbá.Lẹ́yìn ìṣèjọba Odùduwà, Ọbàtálá tún gorí oyè ní ẹlẹ́ẹ̀kejì, wọ́n sì í pín ètò ìṣèjọba láàárín ìdílé Ọbàtálá àti Ọbalúfọ̀n títí Ọ̀rànmíyàn fi da ètò náà rú fúngbà díẹ̀..
wikipedia
yo
Àmọ́, ìṣẹ̀ṣe ìfẹ́ fi hàn pé làjàmi jẹ́ ìran ọ̀rànfẹ́ ní tòótọ́..
wikipedia
yo
Àmọ́, pẹ̀lú ọ̀làjú àti ìkónilẹ́rú, ètò náà yí padà, ó sì pin sí ìdílé mẹ́rin, t í ṣe Ọọ̀ni Ládòdòdò, Ọọ̀ni Òṣìnlá, Ọọ̀ni Ogbòrù àti Ọọ̀ni Gèsì..
wikipedia
yo
Ọọ̀ni tó n jẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí ni Adéyẹyè Ẹnitàn Ògúnwúsì, Oja II (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù Kẹwàá, ọdún 1974).Oríṣiríṣi òǹkọ̀wé pẹ̀lú àtòjọ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ìwé àti iṣẹ́ ìwádìí lóríṣiríṣi ọjọ́ Bada 1954 quotes 15 Names for The Odùduwà tó Lọ̀nmisán Period..
wikipedia
yo
Chief Fetomi 1975 quotes 7 Names for the same Period..
wikipedia
yo
Chief Fṣọgbọ́n 1976 quotes 12 Names For This Period..
wikipedia
yo
Chief awoṣemọ 1985 quotes 22 names from Odùduwà to giesi..
wikipedia
yo
EluYemi 1986 quotes 41 Names From Odùduwà to Nowadays..
wikipedia
yo
orísun fún àtòjọ àkókò a list àwòyínfà, délẹ̀, 1992 pages 30–35.
wikipedia
yo
The prince, from the giesi family, was one of the contenders for the 2015 designation..
wikipedia
yo
See column la.Orísun fún àtòjọ ẹ̀kejì B list ológundu 2008, Pages 58–59..
wikipedia
yo
lists 48 names, that are the b list, except from Ọbalúfọ̀n alayemore (#5) and àwọrokolokin (#12)..
wikipedia
yo
Moreover, ọsin (#18) Is at #25 (Strange Place) Àràbà Adédayo Ológundu was a Native of Ilé-Ifẹ̀, Nigeria..
wikipedia
yo
Lawal 2000, page 21 (Nevertheless, this book is Google described as a 19 pages book !)..
wikipedia
yo
See column lb.Àwọn orísun oríayélujára Source 2015.
wikipedia
yo
This list was already in use before 2015.This làǹfààní kì í ṣe iṣẹ́ tó rọgbọ, ó sì ní àwọn tíwọ́n fi igi láti máa máa fọba jẹ..
wikipedia
yo
ifilelẹ látẹnu awọn afọbajẹ ni ọdun 1980 labẹ section 4(2)..
wikipedia
yo
Ìdí nìyí tí kò fi sí àkọsílẹ̀ déètì tí àwọn Ọọ̀ni ìgbà náà jẹ́..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ déètì bẹ̀rẹ̀ láti ayé Ọọ̀ni Orayégba Ojarẹrẹ.Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àtòjọtún ká (Not Read)àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
OyoTunji Àpéjọpọ̀ Àwọn kan ní yí tí wọ́n ń gbe èdè àti Àṣà Yorùbá láru..
wikipedia
yo
Wọ́n pe ibi tí wọ́n wà ní The Kingdom of OyoTunji, Box 51, Yorùbá Village, South Carolina 29941..
wikipedia
yo
Ilé-Ifẹ̀ ni Ọba yìí ti wá gba Adé ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹfà, ọdún 1981 ni ààfin Ọba Okunade Sijúwadé, Olùbushe keji..
wikipedia
yo
Èyí sì ni ìgbà àkọ́kọ́ tí ẹni tí kìí ṣe ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà yóò gba adé ní Ilé-Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Oriṣiriṣi òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá ni wọ́n ń bọ ní ibi yìí.Àwọn ìtọ́kasí C.m..
wikipedia
yo
Ewì ayaba àti ìlànà ìgbékalẹ̀ láàrín àwọn Ọ̀yọ́ Ọ̀ṣunkí ni ewì Ayaba?Ewì Ayaba jẹ́ ewì tí a mọ mọ àwọn ìyàwó ọba nìkan..
wikipedia
yo
Ọ̀kan pàtàkì lára ẹ̀yà ewì alohùn ilẹ̀ Yorùbá ni pẹ̀lú..
wikipedia
yo