cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ohun tí a ń sọ ni pé àwọn obìnrin nìkan ló ń kópa nínú àgbékalẹ̀ ewì Ayaba.Ọjọ́ ewì Ayaba ti pé láwùjọ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ìwádìí jẹ́ kí a mọ̀ pé irú ewì yìí náà ń wáyé láàrín àwọn Èkìtì..
wikipedia
yo
(Aladesuru, 1985) orúkọ tí a mọ̀ mọ́ ewì yìí ní agbègbè Èkìtì ni Orin Olórí..
wikipedia
yo
Yálà kí a pe ewì yìí ni “ewì Ayaba” tàbí “Orin Olorì”, síbẹ̀ iṣẹ́ kan náà ni wọ́n ń ṣe láwùjọ Yorùbá.Ìwádìí jẹ́ kí a mọ̀ pé àwọn ayaba kì í gbé ewì yìí jáde kọjá àsìkò ayẹyẹ tàbí ìṣẹ̀ṣe inú ààfin ọba láyé àtijọ́..
wikipedia
yo
Lóde òní, ewì ayaba ti ń wáyé nínú ayẹyẹ tó jẹ́ ti ìdílé ọba..
wikipedia
yo
Bákan náà, ewì ayaba a tún máa wáyé nínú ayẹyẹ ìlú; tí ọba bá ti wà níbẹ̀. Nípa àkíyèsí wọ̀nyìí, a rí i pé ewì Ayaba wà fún ọba, ayaba àti ẹbí ọba lápapọ̀.Gbogbo ewì alohùn Yorùbá ló ní kókó tí wọ́n ma ń dá lé lórí..
wikipedia
yo
Lára kókó ti ewì Ayaba máa ń dá lé lórí ni ìjúwe àwọn ayaba gẹ́gẹ́ bí i aya aládé, àrẹ̀mọ ọba tàbí aboṣèlú..
wikipedia
yo
Ìwà òjòwú laarin Ayaba, iṣafihan ipo ọba laarin ilu..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ nípa ìdàgbàsókè tó wọ inú ìlú lásìkò ọba kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ nípa ọdún àti ìbò tó ń wáyé láàrín ìlú tó jẹ́ ti ọba Oyo-Osun..
wikipedia
yo
OyeWale, 'àgbéyẹ̀wò ewi Ayaba laarin àwọn Oyo-Osun'., apileko fún oyè eemẹ́ẹ̀l, Dall, OAU, Ife, Nigeria..
wikipedia
yo
ÀṢAMỌ̀ise yii se agbeyewo ewi Ayaba laarin awon Oyo-Osun..
wikipedia
yo
Ó sì jẹ́ kí a mọ̀ nípa àbùdá ewì ayaba, Lolo-èdè ewì Ayaba, ọgbọ́n ìṣeré ewì Ayaba àti Ìwílò rẹ̀ láwùjọ..
wikipedia
yo
Ọgbọ́n ìwádìí tí a yàn láàyò nínú iṣẹ́ yìí ni gbígba ohun ewì Ayaba sínú fọ́nrán..
wikipedia
yo
Àwọn ìlú marun-un ti àgbà ohun ewì Ayaba wọn sinu fọ́nrán ní Òṣogbo, èdè, ìlawọ́-Ejigbo, ìwọ ati Ikoyi..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, a ṣe àdàkọ ewì wọ̀nyìí, a sì ṣe àtúpalẹ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
Síbẹ̀, a fi ọ̀rọ̀ wá àwọn ọba ìlú tí a mẹ́nubà yìí lẹ́nu wò..
wikipedia
yo
Tíọ́rì ìbára-ẹni-gbépọ̀ láwùjọ ni a yàn láàyò láti fi ṣe àtúpalẹ̀ àkóónú àti lólo-èdè inú ewì Ayaba yìí..
wikipedia
yo
Ìwádìí lórí iṣẹ́ yìí fi hàn pé ewì Ayaba jẹ́ ẹ̀yà lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá tó jẹ́ ti àwọn obìnrin; ní pàtàkì jùlọ ìyàwó ọba olórí ọba tàbí ayaba..
wikipedia
yo
A jẹ́ kí ó di mímọ́ nínú iṣẹ́ yìí pé àwọn ayaba a máa ké ewì wọn yìí láàfin tàbí nínú ayẹyẹ tó kan ọba ìlú dáradára..
wikipedia
yo
A sọ ninu iṣẹ́ yìí pé ìsọ̀rí ayaba meji tí a mọ̀ sí Ayaba Àgbà ati Ayaba Kéékèèké Ló ń lọ́wọ́ ninu ewì yìí..
wikipedia
yo
Ní ìkádìí, iṣẹ́ yìí ṣàlàyé pé orin àti ìṣáré ni ewì Ayaba Ọ̀gun-Ọ̀ṣun..
wikipedia
yo
Ìwádìí lórí iṣẹ́ yìí sì jẹ́ kí a mọ̀ pé ewì Ayaba yìí gbajúgbajà nínú ṣíṣe ìjíyìn nípa ayaba, ọba àti àwọn ìṣẹ̀ṣe inú àwùjọ kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
Baṣọ̀run Oluyọlé jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú àwọn jagunjagun tí ó wá láti ìlú Ọ̀yọ́ Ọ̀yọ́ sí ìlú Ìbàdàn.Wọn bí Baṣọ̀run Oluyọ ni Ọ̀yọ́ àtijọ́ sí inú ìdílé Olúwàoyè tí bàbá rẹ̀ sí jẹ́ àrẹ̀mọ Aagbọ̀nyín tí ó jẹ́ ọmọ Aláàfin Abiodun nígbà náà ..
wikipedia
yo
Oun ni o kọkọ ri ilu Ibadan gẹgẹ bi ilu olokiki yatọ si ibudo ogun..
wikipedia
yo
Ìdí rèé tí ó fi fi ìdí ìjọba tó Giriki múlẹ̀ nígbà náà..
wikipedia
yo
Àsìkò rẹ ni àwọn ìlú tí wọ́n wà ní abẹ́ Ìbàdàn gbèrú sí..
wikipedia
yo
Kò kùnà lati gbé iṣẹ́ àgbẹ̀ lárugẹ, bẹ́ẹ̀ ni o fi ìpìlẹ̀ ọrọ̀ ajé tí ó nípọn múlẹ̀..
wikipedia
yo
Ìdí rèé tí a fi ń pe Ìbàdàn ni “Ilé Olúyọ̀lé”.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí jagunjagun látàrí houʹtos houʹtos tí ogun dá sílẹ̀ láàárín àwọn àgbààgbà olóyè ìlú Ọ̀yọ́-ilẹ̀ láti gorí apẹ̀rẹ̀ Aláàfin ti Ọ̀yọ́ nígbà náà tí ó ṣófo, èyí ni ó mú kí wàhálà bẹ́ bẹ́ sílẹ̀ láàárín Aláàfin àti Baṣọ̀run Gáà ti ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ Ọ̀yọ́ ìgbà náà sá àsálà fún ẹ̀mí ara wọn..
wikipedia
yo
Fifọ́nká tí àwọn ọmọ Ọ̀yọ́ fọ́n ká yí, tí wọ́n sì ti lọ tẹ̀dó sí oríṣìíríṣìí ibùgbé tí wọn kò sì fẹ́ san ìṣákọ́lẹ̀ fún Ọ̀yọ́ mọ́, àsìkò yìí ni ìbá Olúyọ̀lé di lààmì-laaka láàrín àwọn jagunjagun..
wikipedia
yo
Ó kọ́kọ́ di ìlúmọ̀ọ́ká látàrí ipa tí ó kó láàarín àwọn ọmọ ogun tí wọ́n borí ogun Owu, ní èyí tí ó sì mú kí ìjọba ilẹ̀ Ẹ̀gbá àti àwọn ìlú bí Ìbàdàn ó ṣubú..
wikipedia
yo
Láti bu ọlá fún pẹ̀lú ipá rẹ̀ láti lè jẹ́ kí ìjọba Ọ̀yọ́ tí ó ti ń dẹnu kọlẹ̀ ó tún gbiná ya nínú àwọn ogun tí ó mú Ọ̀yọ́ borí ilẹ̀ Ẹ̀gbá, Ìjẹ̀bú-rẹ́mọ yí ni ó mú kí wọ́n fi jẹ́ ''Ààrẹ àgọ́ ilẹ̀ Ìbàdàn’’..
wikipedia
yo
Oun naa si fi ara rẹ jẹ oye ''O-kakanfo’’, ti o so o di Ologun apàṣẹ wàá kẹta fun ilé Ìbàdàn.Ìwé Àmúlò Akínwùmí Atanda (200) Baṣọ̀run Oluyọlé Ìbàdàn; Rasmed, Ntab 978-80-24-0..0-0..
wikipedia
yo
Kúròwábu kan ní ila-oorun gusu ilẹ̀ Pólándì ni ó ń jẹ kúròw..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ ni wọ́n ti ń ta àwọn oúnjẹ tí wọn ń pèsè ní agbègbè rẹ..
wikipedia
yo
Àwọn ilé-iṣẹ́ tí wọ́n ti ń fi awọ ẹran ṣe nǹkan wà ní ibẹ̀ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
Ní sétúrì kẹrìndínlógún, ibẹ̀ ni àwọn tí ó ń ṣe kafinisíimú (Caligism) ti máa ń pé jọ nítorí pé ibẹ̀ ni àwọn kan tí wọ́n ń pe ‘Polish Brethren’ máa ń gbé..
wikipedia
yo
Nígbà tí yóo fi di ọdún 1660, ọpọlọpọ ninu àwọn eniyan ibẹ̀ ti yí pada sí ẹṣin Ariànísíimú (Arianism)..
wikipedia
yo
Ìran Yorùbá, àwọn ọmọ Yorùbá tàbí ọmọ Anti-oòjíire, jẹ́ ara ìpínlẹ̀ ẹ̀yà, ní apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Áfríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n jẹ́ ara ìpín àwọn ìran tó pọ̀ jù ní orílẹ̀ Áfríkà..
wikipedia
yo
Ẹ lè rí wọn ní ìpínlẹ̀ púpọ̀ bíi ìpínlẹ̀ Edo, Ìpínlẹ̀ Èkìtì, Ìpínlẹ̀ Èkó, Ìpínlẹ̀ Kwara, Ìpínlẹ̀ kogi, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Ìpínlẹ̀ Oǹdó, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, àti ní ẹ̀yà ìlà owó òsì ti ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ẹ tún lè rí wọn ní ìpínlẹ̀ tó wà ninu orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin (Dahomey), ní orílẹ̀-èdè Saró (Sierra Leone), ati ní àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn bíi àwọn tí wọ́n pè ní Togo, Brazil, Cuba, Haiti, Amẹ́ríkà ati Venezuela..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá wa l'ara àwọn tó tóbi jù ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó lé jẹ́ pé àwọn lọ́pọ̀ jù, àbí kí wọ́n jẹ́ ikeji, tabi ẹ̀yà kẹta tí wọ́n pọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Àwọn Yorùbá jẹ́ àwọn ènìyàn kan ti èdè wọn pín sí oríṣiríṣi..
wikipedia
yo
Àwọn ìpínsísọ̀rí yí ni à ń pè ní ẹ̀ka èdè tàbí èdè àdúgbò.Ìran Yorùbá jẹ́ ènìyàn kan tí wọ́n fẹ́ràn láti máa ṣe aájò àti àlejò àwọn ẹlẹ́yà míràn, wọ́n sì ma ń nífẹ sí ọmọ'kejì.Èdè èdè Yorùbá jẹ́ èdè tí àwọn ìran Yorùbá ma'n sọ sí ara wọn..
wikipedia
yo
Ẹ lè ri èdè yi ni ilẹ̀ Nàìjíríà, ilẹ̀ Benin, àti ni ilẹ̀ Togo..
wikipedia
yo
Iye tó'n sọ èdè yí ju ní gbogbo ilẹ̀ Yorùbá 30 Bellli lọ.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ará NàìjíríàYorùbáAM..
wikipedia
yo
Ẹgba Owólélẹ̀ Ọlájubù Aeyegírìiwe Àṣà Ìbílẹ̀ Yorùbá ti Olóyè olùdáre Ọlájubù jẹ́ olóòtú, ojú-ìwé 1–11, Ikeja; Longman Nigeria Limited, 1975..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí a ti ńní ilé ní ẹ̀kún ẹ̀gbà ọwọ́dé; ojú-ìwé 113-119.agbègbè kọ̀ọ̀kan ni ó ní òfin àti àṣà nípa bí ènìyàn ṣe le ní ilé fún ìgbà díẹ̀ tàbí fún ìgbà pípẹ́..
wikipedia
yo
Ní àwọn agbègbè ti ọ̀làjú ti gòkè ní gbogbo àgbáyé, ilẹ̀ nínú ṣe pàtàkì fún àǹfàní iṣẹ́ẹ jíjẹ, mímu àti ọwọ́ nìkan..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ òṣèlú kò ṣe dandan lóríi rẹ̀ bíkòṣe ninu àwọn ọ̀ràn tí ó da ìlú meji pọ̀..
wikipedia
yo
Láti ilẹ̀ wa láàrin àwọn Yorùbá, ilẹ̀ nínú ṣe pàtàkì fún àǹfàní jíjẹ, mímu àti ti ọwọ́..
wikipedia
yo
Láti kọ́lé àti láti ṣe ọkọ ni ó nmú kí gbogbo ènìyàn ní ìfẹ́ láti ní ilẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ìwọ̀n ìgbà tí ó jẹ́ iṣẹ́ àgbẹ̀ ní kókó iṣẹ́ẹ wa, àwọn olóyè tàbí àwọn ọba ìlú tí wọ́n ní ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn lábẹ́ ìjòyè wọn máa ńní ilẹ̀ tó pọ̀ ní ìkáwọ́ọ wọn ju ẹlòmíràn tí ẹbíi rẹ̀ kéré..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn tó wà lábẹ́ àṣẹ olóyè kan, tí wọ́n sì ṣiṣẹ́ sìn í ti pọ̀ tó ní iyì àti ẹẹ rẹ̀ ṣe máa pọ̀ tó láàrín ẹgbẹ́ àti ìlú..
wikipedia
yo
Èyí ni ó mú ọ̀rọ̀ àwọn àgbà kan wá tí ó sọ pé, ‘Ohun tó wunni ní npọ̀ nínú ọ̀rọ̀ ẹni, ológun ẹrú kú, aṣọ ọ̀ rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan.” Ọ̀nà tí ìjòyè yìí fi le di aláṣẹ lórí àwọn irú ènìyàn wọ̀nyí ni nípa fífi ilẹ̀ fún àwọn ẹbí tàbí ìdílée rẹ̀, ìbátan tàbí àlejò fún ọ̀gbìn ṣíṣẹ́ àti àwọn nǹkan míràn gbogbo, àti nípa pínpín oríṣiríṣi ẹ̀bùn lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan láàrin àwọn ènìyàn wọ̀nyí..
wikipedia
yo
Lílo ilẹ̀ tí a tọrọ yìí lè jẹ́ fún ìgbà díẹ̀ tàbí fífún láyéláyé..
wikipedia
yo
Fun idi eyi, a ni lati ri i pe ki i se fun iyi laarin ẹgbẹ tabi ilu nikan ni o mu ki awon idile oloye kan maa ni ile to po, sugbon eyi je ona lati pin nnkan jijẹ, mimu ati ti owo ti o won eyiyii ni ile, ni ona ibamu pẹlu Ife múra eniyan ti o wa ni ilu tabi Abule..
wikipedia
yo
Nítorí náà, bi a bá wò ó lati ìhín lọ, ó ṣe é ṣe ki a sọ̀rọ̀ ilẹ̀ nini laarin àwọn Yorùbá lati ipa jijẹ, mimu àti ti owó..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n a ó mẹ́nu ba díẹ̀ nínú ètò ìlú ṣiṣẹ́ àti ẹgbẹ́ kíkó tí ó bá jẹ mọ́ ti ilẹ̀ nínú..
wikipedia
yo
Ìdá-helpìranraẹnilọ́wọ́ Ọlájubù _*Ọjọ́ Àṣà Ìbílẹ̀ Yorùbá ti Olóyè olùdáre Ọlájubù jẹ́ olóòtú, ojú-ìwé 1–11, Ikeja; Longman Nigeria Limited, 1975.Ọ̀jọ̀gbọ́n Aṣèrántí Ọjọ́..
wikipedia
yo
Àṣà ìran-ara-ẹni-lọ́wọ́; ojú-ìwé 158-164.Gẹ́gẹ́ bí gbogbo wa ṣe mọ̀ láti ọjọ́ tí aláyé ti dáyé ni àwọn èèyàn ti nràn ara wọn lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Bí a bá ńsọ̀rọ̀ nípa ọjọ́ tí àlàyé ti dáyé àwọn ti ńká ìwé Bíbélì lára wa á fẹ́ mú ọkàn wọn lọ sí àkókò tó jẹ́ pé ọkùnrin kan ṣoṣo ló wà lórílẹ̀ èdè ayé yìí, èyí ni Ádámù..
wikipedia
yo
Mo rò pé a ò mọ gbogbo iṣẹ́ tó ṣe nínú ọgbà tí ó wà, ṣùgbọ́n tí ó bá ṣe ẹni tí ó mọ oúnjẹẹ jẹ níb í èèyàn bíi tiwa ni, ó dáni lójú wí pé yíò máa gbìyànjú láti fi owó ká èso igi jẹ ni..
wikipedia
yo
Oúnjẹ sì nìyí kì í dùn tó bẹ́ẹ̀ tó bá ṣe èèyàn nìkan ṣoṣo ló ńjẹ ẹ́ láàrọ̀, lọsàan ati lálẹ́ láti ọjọ́ kan dé ọ̀sẹ̀ kan, dé oṣù kan, dé ọdún kan..
wikipedia
yo
Ìtàn Bíbélì náà sọ fún wa pé nígbà tí ó bùṣe, Olúwa fi olùrànlọ́wọ́ kan jíńkí rẹ̀, eléyìí náà ni obìnrin tí a npè ní ẹẹ́fà..
wikipedia
yo
Ó dà bí ẹni pé inú ọgbà idẹni náà gbádùn sí i lẹhìn tí àwọn méjèèjì ti wà níbẹ̀..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n oríṣi ìrànlọ́wọ́ tí wọ́n rí náà kì í ṣe nkan tí kò ní ní ìfàsẹ́hìn-in tirẹ̀..
wikipedia
yo
Mo fi ìyókù sí ọkàn ẹ̀yin tí ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìwée ti Bíbélì..
wikipedia
yo
Ohun tí mo fẹ́ fàyọ nínú ìfisíwájú ọ̀rọ̀ mi yìí ni pé ọwọ́ kan kò gbé ẹrù dé orí, a sì ti mọ̀ dájú pé bí ọwọ́ ọmọdé kò ṣe to pẹpẹ bákan náà ni ọwọ́ àgbàlagbà kò ṣe wọ àkèrébẹ̀..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn olóye èèyàn ṣe máa ńsọ fún wa nígbà gbogbo pé ‘òsì wẹ ọ̀tún ọ̀tún wẹ òsì òun ni ọwọ́ fi nmọoṣù
wikipedia
yo
Lọ́rọ̀ kan àwọn èèyàn ilée Yorùbá ti gbà á ní àṣà kan pàtàkì pé a ní láti máa ran ara wa lọ́wọ́, kò tó diìrù ẹ a lè dá ohunkóhun oníyebíye kankan ṣe..
wikipedia
yo
Ni ìṣẹ̀dálée wá àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin tó bá ti nfẹ aya, wọn a máà ran òbi àfẹ́sọ́nà wọn lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Kó tó tilẹ̀ dimá ẹ̀ á bẹ̀rẹ̀ sí í ná owó, èèyàn yíò tín á ara ṣáájú-ṣáájú..
wikipedia
yo
Èyí nipé e àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀ lè máa bá àna wọn lọ sí oko láti kọ́lé tàbí láti tún ohun ọ̀gbìn-in wọn ṣe..
wikipedia
yo
Bákannáà ni wọ́n nṣe ìrànlọ́wọ́ nínú ilé láti kọ́ ilé tuntun tàbí láti tún ilẹ̀ tí ó bá ḿbàjẹ́ ṣe, bóyá ó njó ní, tàbí ìgànná rẹ̀ ńfẹ́ kí a túbọ̀ gbé òun dúró dáadáa..
wikipedia
yo
Ju gbogbo rẹ̀ lọ, nígbàkugbà ti wọn bá ti ńṣe irú iṣẹ́ bi eléyìí kìí ṣe ẹni ti ó nfẹ àfẹ́sọ́nà nikan ṣoṣo ló ńṣe iṣẹ́ bi eléyìí......
wikipedia
yo
Oǹdó jẹ́ ìlú ní ìpínlẹ̀ Oǹdó ni Nàìjíríà.Kí a tó rí wákàtí Mjì lẹ́hìn tí a ti gúnlẹ̀ sí Okitipupa, a ti dé Òndó..
wikipedia
yo
Ti enia bá kọ́kọ́ ri àwọn ilé nlá nla ti ó wa li apá ọ̀tún àti li apá òsì titi, oluwa rẹ yio ṣebi igboro Èkó li on wa..
wikipedia
yo
Ti enia BAS i yi ile oja awon oyinbo onisowo ati awon isongbe ke-ke-ke kakiri daradara, yio mo pe ilu onisowo pataki kan li Ondo je larin awon ilu nla nla ile Yoruba..
wikipedia
yo
Ilé ọ̀kan ninú àwọn gbajúmọ̀ ilú ti ó jẹ́ oníṣòwò li a wo si li ọjọ́ ti a dè Ondó..
wikipedia
yo
Nigbati o di alẹ, ti a jẹun tan, ti a ntag, li ọ̀kan ninu àwọn ọ̀rẹ́ mi bèrè lọ́wọ́ balẹ ilé wa, o ni, ‘Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ma pe mo ntọ́pínpín o, owó kílí ẹ̀nyín ará Òndó ńṣe tí ẹ fi lí owó lọ́wọ́ tó báyĩ, tí ilé mèremère sì fi pọ̀ ní ìlú nyín tó báwọ̀nyí?”E.L. Láṣebìkan (1956), London; Ojúlówó Yorùbá Ìwé kini Oxford University Press..
wikipedia
yo
Ojú-ìwé = 434.Ọ̀rọ̀ nípa dùndún tí ó jẹ́ ìlú kan pàtàkì ní ilẹ̀ Yorùbá ni òǹkọ̀wé yìí sọ̀rọ̀ lé lórí..
wikipedia
yo
Ó mẹ́nu ba ipò dùndún nínú àṣà Yorùbá, ìtàn tí ó jẹ mọ́ dùndún, ibi tí a ti máa ń lò ó tí ó sì fi ibi àṣeyẹ kan ṣe àpẹẹrẹ..
wikipedia
yo
Ó sọ̀rọ̀ nípa bí wọ́n sen sè é àti àwọn ìlù mìíràn tí wọ́n máa ń lù mọ́ ọn..
wikipedia
yo
Akin EUBA (born Ọlátúnjí Akin EUBA, Lagos, Nigeria, April 28, 1935)Iṣẹ́ Akin EUba ni òǹkọ̀wé yẹ̀ wò nínú iṣẹ́ rẹ̀ yìí..
wikipedia
yo
Lóòótọ́, ìlànà àwọn ńgẹ̀ẹ́sì ni Akin EUba fi n kọrin ṣùgbọ́n àṣà àwọn Yorùbá ni ó gbé iṣẹ́ rẹ̀ ka..
wikipedia
yo
Òǹkọ̀wé yìí sọ̀rọ̀ nípa ìwádìí tí Akin EUba ṣe lórí ìlú..
wikipedia
yo
Yunifasiti Obafemi Awolowo je Yunifasiti ijoba apapo ni Naijiria to bùdó si Ile-Ife..
wikipedia
yo
Wọ́n da ilé-ẹ̀kọ́ yí sílẹ̀ ní ọdún 1961, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ níbẹ̀ ní oṣù kẹwàá ọdún 1962àwọn ìtọ́kasí Yunifásítì ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Felix AbiDemi Fikun jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n (Professor) Nínú ìmọ̀ Ẹ̀dá-Èdè (lingistics) àti Èdè Yorùbá (Yorùbá Language) ní Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ Ẹ̀dá-Èdè àti àwọn èdè Adúláwọ̀ (Department of lingistics and African languages) ní Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ní Ilé-Ifẹ̀ , Nigeria..
wikipedia
yo
Àpilẹ̀kọ rẹ̀ dá lórí mófoli, ẹ̀ka-èdè Yorùbá kan tí wọ́n ń sọ ní ilé Bene (Benin Republic)..
wikipedia
yo
Àkòrí ìwé àpilẹ̀kọ àkọgboyè náà ni “Àsìkò àti Ìbà-Ìṣẹ̀lẹ̀ Nínú Ẹ̀ka-Èdè Yorùbá Oluwli” (Tense and Aspect in the Olumófoli Dict of Yoruba)..
wikipedia
yo
Lọ́dún 1998 ló gba oye ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ Kejì (MA Yorùbá Language); bákan náà ló tún gba oyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ kejì mìíràn (MA lingistics) lọ́dún 2004 ní Yunifásítì ìlú Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University ló ti gba oye Ọ̀mọ̀wé (PhD Yoruba language & lingistics) ni 2006..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2013 ni Felix AbiDemi Fikun di ọ̀jọ̀gbọ́n ní Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University, Ilé-Ifẹ̀, Nigeria..
wikipedia
yo
Òun náà ló tún gbégbá orókè jù lọ láàrin àwọn akẹ́kọ̀ọ́ kíláàsì rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó di olórí ẹ̀-ẹ̀kọ́ (HodHod) ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè àti èdè Adunlẹ̀ (acting head, Department of lingis and African languages) OAU Ile-Ife lodun 2007..
wikipedia
yo
"A G£g StRCf of Aspect in Yoruba-Akoko-Akoko", in Current perpersona in syntax and dialelogy, Pages 156-191.2009..
wikipedia
yo