cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Anne's School, Ibadan àti Abeokuta Grammar School.Ọmọ ẹ̀yà Yoruba ni Aderonkeàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Genilase dibaba Keneni ni a bini ojo kejo, osu February, odun 1991 je elere sísá lobinrin ile Ethiopia to da lori arin ati ona jinjin.Ni odun 2008, Genila yege ninu idije to si20 to si gba ami ti ola ti ola ninu mita ti egberun laarin..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2009 dé 2017, Genilaẹbẹ kópa nínú ìdíje àgbáyé tó sì tún kópa nínu àṣeká àwọn eré ṣísá náà.Ni ọdún 2010, dibàbá kópa nínú ìdíje àgbáyé U20 lápapọ̀ tó sì gba Wúrà ní mita ti ẹgbẹ̀já máà.Ní ọdún 2014, dibàbá ni a peni elerelobinrin ti Laureus fún ọdún náà.Ni ọdún 2015, dibaba jẹ́ eléré sísá lóbìnrin ti IAAF àgbáyé ti ọdún náà.Ní ọdún 2015, Gense kópa nínu ìdíje àgbáyé tí mita ti ẹgbẹ̀rún máàrún tó sì gba àmì ẹ̀yẹ ti ọ̀la ti idẹ àti wúrà nínú ayẹyẹ náà.Ní ọdún 2016, Gense kópa kópa nínu Olympics ti Rio tó sí gba àmì ẹ̀yẹ ti ọ̀la ti Silver ní mita ti ẹgbẹ̀rún kan àti aadọrun.
wikipedia
yo
Edu (ti a bi ni ọjọ ketadinlogbon Oṣu Kẹwa ọdun 1986) jẹ oloselu ọmọ orilẹ-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni Komisona fun Eto Ilera Ara ni Ipinle Cross River ati Alaga Ẹgbẹ Awọn Komisona ni Orilẹ ede Naijiria.Awọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
ọjọ́ ìbí ni àjọ̀dún ọjọ́ pàtó tí a bí ẹnìkan.Gẹ́gẹ́ bí arákùnrin Simon Jacobson ti ṣe lálàyé, ó dára kí a máa dunnú fún àwọn ohun tí a jẹ́ láyé àti ohun tí àti gbé ilé ayé ṣe..
wikipedia
yo
Ṣugbọn kí àwa tó leè máa ṣe eléyìí, a ní láti kọ́ mọ rírì ibi wa gan an.Ibi ni ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé ẹ̀dá..
wikipedia
yo
Ohùn ní fèrèsé sí ìgbé ayé ẹ̀dá, láti lè ní àbáyọrí ipa rẹ̀..
wikipedia
yo
Nitorina ọjọ ibi jẹ akoko kan pataki, to yẹ ki a ya sọtọ fun ra ẹni, bi ẹni ya ojo idasilẹ orilẹ-ede tabi ọjọ ti a ṣẹda ile-iṣẹ kan..
wikipedia
yo
O tun jẹ akọkọ lati ranti awọn iṣẹlẹ pataki to ti ṣẹlẹ..
wikipedia
yo
Lati ṣe àjọyọ̀, idúpẹ́ àti atún gbéyẹ̀wò bi a ti ṣe nlo ayé wa dáradára si.Nitori àkókò àti igbà a maa yi, àwọn nkan pàtàki a máà wáyé ni àkókò ọjọ́ ìbí rẹ lododun..
wikipedia
yo
Irúfẹ́ okùn kan náà ti Ṣáwọn fi kún ọ yóò tún ru ọ́ sókè ní àkókò yí..
wikipedia
yo
A lè ṣe èyí nípa jíjọ̀wọ́ ara wa fún kunkun wa àti láti lo àwọn ẹ̀bùn àti ohun tí ó wà ní ìkáwọ́ wa láti ṣe ara wa àti alábágbé àyíká wa àti gbogbo or=lé àgbáyé lóore bí ìṣekùn tí ń fẹ́.Ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ni a fi ń ṣe àjọyọ̀ ibi fún ra rẹ̀, àti ayọ̀ ìwàláàyè..
wikipedia
yo
O sì tún jẹ́ àkókò láti tún inú wa rò lọ ríi, kí ni ìpààlà lãrín àwọn àṣeyọrí tí àtiṣe àti àwọn tí a tún leẹsẹ̀? Ṣé mo n lo àkókò mi dáradára tàbí mi ó sì ní ojú ọ̀nà gaan tí ó yẹ kí ó wà? Báwo ni mo ṣe lè mú èrò àti ìṣe mi dọ́gba?Ọjọ́ ìbí tún lè mú wá ní àròjinlẹ̀ nípa ohun tí ibi ènìyàn jẹ́.Láti rántí ọjọ́ ìbí jẹ́ ànfàní láti pinnu ìbéèrè ìgbé-ayé tuntun..
wikipedia
yo
Kò ní fiṣẹ́ bí ohun kan ti rí Lanààbọ̀, tàbí ní àkókò díẹ̀ sẹ́hìn, gbogbo ìgbà ni a máa ní ọ́re-ọ̀fẹ́ àti tún ìtàn ayé wa kọ́..
wikipedia
yo
Ọjọ́ ìbí a máa túnilára, a máa fun ni ní ọ́re-ọ̀fẹ́ láti ṣe àgbékalẹ̀ ayé ara ẹni..
wikipedia
yo
Kìí ṣe ni tí àwọn nkan àfọwọ́bá nìkan, ṣùgbọ́n pẹ̀lú àwọn ohun tí nṣe tèmi.Ó leè kó mọ̀lẹ́bí àti àwọn ojúlùmọ̀ rẹ̀ jọ ní ọjọ́ ìbí rẹ̀ kí ẹ jùmọ̀ ṣe ìgbélẹwọ àwọn ohun tí ó ṣe ànfàní tí ó sì ṣe pàtàkì.Kò wá sí ohun tí ó dára tó kí a ṣe ọjọ́ ìbí pẹ̀lú ọkàn ìṣoore..
wikipedia
yo
Tí a bá fẹ́ fi ọkàn ọpẹ́ wa hàn ìbá dára kí a ṣe pẹ̀lú ohùn árítọ́kasí rere kan, ní lílétí a kò tilẹ̀ ṣeé lànà tàbí pé ṣe ní a fi ipá mú wa, tàbí pé ẹnìkan ni ó tọ́ka rẹ̀ síwá..
wikipedia
yo
Ṣugbọn tí ó jẹ́ ohun tí ó wá láti inú ọkàn ẹni láti dúpẹ́ ibi ati ìdásí wa.Irúfẹ́ nkan báyìí a máa mú inú ẹlẹda ẹni dùn..
wikipedia
yo
Eyi gan ni iriri otitọ pe abíniwaye.awọn itọkasiawọn ọjọobi..
wikipedia
yo
Michelle Abueng tí a bí ní ọjọ́ kẹfà Oṣù Kaàrún Ọdún 2001 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède Botswana kan tí ó mú ipò iwájú lórí pápá fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Zambia FC Yasa FC àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin ti orílẹ̀-ède Botswana .Ó di ẹni tí ẹgbẹ́ Zambia Yasa Queens mọ́ nígbà tí ó ń gbábọ́ọ̀lù tako ZAMBIA ní bí bí African U-17 Women's World Cup jáw Tournament ti ọdún 2018, ṣùgbọ́n wọ́n kò ní Yetoted láti buwọ́ lùú gbígbá wọlé rẹ̀ títí di ọdún 2019 nítorí ó jẹ́ ọmọde ní àkókò náà..
wikipedia
yo
Ó mi àwọ̀n pẹ̀lú àmì ayo máàrún nínú eré bọ́ọ̀lù tí ó gbà tako Nàkòjì ní bí ìdíje ayẹyẹ ìfẹ́ àgbáyé tí àwọn obìrin U-20 ti ọdún 2020 .. )
wikipedia
yo
Ó ṣe àkọ́kọ́ ifarahan ti òkè-òkun ní bi ìdíje 2019 COSAFA Women's Championship ní ọjọ́ Kínní Oṣù Kẹjọ Ọdún 2019àwọn Ìtọ́kasíita ìjápọ àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 2001..
wikipedia
yo
Lone Gaọ̀fẹ́togé tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógun osù keje ọdún 2001 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-èdè Motswana kan tí ó mú ipò olùgbèjà lórí pápá fún gẹ́rọ́nà àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù ti àwọn obìnrin ti orílẹ̀-èdè Botswana .Àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 2001..
wikipedia
yo
Nondi Mahláṣẹla ti a bi ni ọjọ karundinlogbon oṣu kejila ọdun 1991 jẹ agbabọọlu aláfẹsẹ̀gbá ti orilẹ-ede Motswana kan ti o mu ipo iwaju lori papa fun Prison ati ẹgbẹ agbabọọlu awọn obinrin ti orilẹ-ede Botswana .wo eleeyi naa Akojọ awọn agbabọọlu agbaye ti awọn obinrin Botswanawọn itọkasi awọn eniyan Alààyèawọn Ọjọ́ìbí ni 1991..
wikipedia
yo
Leori Gloria Moeng tí a bí ní ọjọ́ kẹta Oṣù Kínní ọdún 1998 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède Motswana kan tí ó mú ipò Pilélé lórí pápá fún Bdf àti ẹgbẹ́ àwọn obìnrin orílẹ̀-èdè Botswana .iṣẹ́ ẹgbẹ́ Moeng ti gbábọ́ọ̀lù fún Galarọ́nà ní Botswana.Iṣẹ́ Òkè-òkun mọ́eng dúró fún Botswana ní ìpele àgbà ní àkókò ìdíje COSAFA Women's Championship ti ọdún 2021 àti Africa Women Cup of Nation qualification ti ọdún 2022 . Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyè Ọjọ́ìbí ní 1998..
wikipedia
yo
OluFúnkẹ́ Adeboye jé ojogbon ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ẹ̀ka fún ìtàn ní Yunifásitì ìlú Èkó, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Òun ni adarí Faculty of Arts Ile-iwe naa lọwọ lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Àwọn nkan tí Adeboye fẹ́ràn láti ma ṣe ìwádìí nípa ni ìtàn Nàìjíríà kí ó ti pe àwọn òyìnbó amúnisìn kó Nàìjíríà lẹ́rú, nígbà tí wọ́n kó lẹ́rú àti nípa bí ìjọ Pentecostal ṣe gbilẹ̀ ní ìwọ̀ Oòrùn Africa.Ìpilẹ̀ a bí OlúFúnkẹ́ Adeboye (orúkọ àbísọ rẹ̀ ní ọjọ́) ní Ìbàdàn, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O lo ile iwe Our Lady's Girls' High School, Ilé-Ifẹ̀, ní Ìpínlẹ̀ Osun, Nàìjíríà ní ọdún 1983..
wikipedia
yo
O lo Yunifasiti ilu Ibadan, Naijiria nibi ti o ti gba ami eye Bachelor of Arts (B.A.A), Masters of Arts (M.A. ati Dókítà(PhD) ninu imo itan ni ọdun 1988, 1990, ati 1997..
wikipedia
yo
O bẹrẹ iṣẹ gege bi igbakeji olukọ ni Yunifasiti Ipinle Ogun (ti oruko re ti yi pada si Olabisi Onabanjo University), ago iwoye, Naijiria ni ọdun 1991..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1999, ó lọ sí ẹ̀ka ìtàn ní Yunifásítì ìlú Èkó gẹ́gẹ́ bi olùkọ́, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí n gòkè nínú iṣẹ́ rẹ̀ kí a tó sọ di ọ̀jọ̀gbọ́n ní Oṣù kẹta ọdún 2011.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Aisha Lawal Ọládunni jẹ́ òṣèré Nàìjíríà, ònkọ̀wé àti òṣèré fiimu...
wikipedia
yo
Arabinrin naa ni won yan fun ami eye osere ti o ni ileri julo (Yoruba) ni odun 2014 City People Entertainment Awards, osere ti o dara julo ninu Ikópa re gege bi Aṣaaju (Best Actress in leading Role – Yoruba) Ami eye ni odun 2015 Best of Nollywood Awards, Best Indigenous language Movie/tv series (Yoruba) ni Awards Africa Magic Viewers' Choice Awards 2016 ati oṣere ti o dara ju ti ọdun (Yoruba) ati oṣere atilẹyin dara julọ ti ọdun (Yoruba) ni ọdun 2018 City People Movie Awards..
wikipedia
yo
</Ref>ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ aye rẹ Aisha Lawal je omo bibi ilu Ibadan, Ipinle Oyo, ni ile Naijiria..
wikipedia
yo
Ó sì lọ sí adéen International School àti Federal Government College, Ògbómọ̀sọ́..
wikipedia
yo
Aisha Lawal ní itara láti ṣe ìṣeré láti ìgbà èwe rẹ̀, níbi tí yóó ṣe ní orírírí àwọn eré orí ìtàgé..
wikipedia
yo
lẹ́hìn náà Lawal lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Lead City, níbití ó ti gba oyè ní òfin àti òye kejì ní ìṣàkóso gbogbo ènìyàn (Public Administration).Iṣẹ́ rẹ̀ Aisha Lawal ló sì "Femi Adebayo's J15 School of Performing Arts" láti ọdún 2008 sí ọdún 2010 ó sì kọ́ bí a ṣe lè ṣe eré..
wikipedia
yo
fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ ni ‘Adùn-má-dé’ níbí tí ó ti ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó..
wikipedia
yo
Láti ìgbà tí ó ti di olókìkí, ó tẹ̀síwájú láti ṣe eré ní àwọn fiimu tí ó ju ọgọ́rùn-ún lọ..
wikipedia
yo
O ti gbé fiimu to bi mẹ́wàá jáde gẹ́gẹ́ bi ìmú níkà àti ọpọ́n Ifẹ̀..
wikipedia
yo
Láìpẹ́, ó ṣàfihàn nínú Love Castle (2021) àti fíìmù Netflix ti Kunle Afolayan, Anikulapo (2022) bi i Olorì Súnkànmí.Ayé rẹ̀ Aisha Lawal wá láti Ìdílé tí ó ní ọmọ mẹ́ta àti pé òun ní Ọmọ Kejì..
wikipedia
yo
ó jẹ́ mùsùlùmí.Àwọn fíìmù rẹ̀ King of bókú (2022) Anikulapo (2022) Love Castle (2021) Survival of Jelili (2019) blog's Wife (2017) SIMbi alámàlà erégún JáKànbru Aiyepe Aapala ìyàwó kan ó Dilemma Shadow Nkan inu igi Irúgbìn Aiku|dèkéàwọn Itoka sí..
wikipedia
yo
Christie Ade Àjàyí (tí a bí ní ọdún 1930) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ń jà fitafita fún kíkọ́ àwọn ọmọdé bí a ti ń kàwé láti ìgbà tí wọ́n ti wà ní ọmọ jòjòló..
wikipedia
yo
Ó ti kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé ní èdè gẹ̀ẹ́sì fún àwọn ọmọdé, àwọn ìwé rẹ̀ sì jẹ́ ìwé nípa Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ olùkọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, ó s jẹ́ ọmọ àwọn ẹgbẹ́ gbẹ́jọ́ tí ó ń bìkítà fún ètò ẹ̀kọ́ àwọn ọmọdé.Ìtàn wọn bí Christie Àdùkẹ́ Martins ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹta ọdún 1930 ní ilé Olúji, ìpínlẹ̀ Òndó, Christie Adé Àjàyí (tí wọ́n tún lè kọ́ bí Adé-Àjàyí) ló sì kúkọ́ Girls' School ní ìlú Ìbàdàn (tí àwọn ènìyàn wa padà mọ́ sí St..
wikipedia
yo
Anne’s School), lẹ́yìn náà, ó lọ sí United Missionary College, Ìbàdàn níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ láti di olùkọ́..
wikipedia
yo
Ó tún tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní fronẹ̀bẹ̀l Institute, London àti ní Institute of Education níbi tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ diploma nínú ìmọ̀ títọ́ àwọn ọmọdé ní ọdún 1958..
wikipedia
yo
Laarin odun 1952 si 1978, o ko awon ni opolopo ile-iwe ni Naijiria ati ni ile-iwe kan ni London, nibi ti o ti di olori ile-iwe naa headmistress, o tun te eko re siwaju ni San Jose State University, California..
wikipedia
yo
Ade Ajayi ni ọdun 1956, awọn mejeeji si bi ọmọ marun-unàwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Ummi Ibrahim jẹ́ òṣèrébìrin kannywood(an Hausa language cinema) tó di olókìkí nínu fíìmù jíǹsì níbi tí ó ti ní orúkọ rẹ̀ ní Zayoté..
wikipedia
yo
.Iṣẹ́ rẹ̀ àríyànjiyàn wà nípa òṣèré náà ní ilé-iṣẹ́ náà bí ó ṣe sọ pé òun lòún ga jùlọ..
wikipedia
yo
Eyi fa ìfarapa laarin awon elegbe rẹ lati igba ti won ti rii kẹhin ni kannywood ni ọdun 2006.Awon fiimu rẹ jíǹsìFlag of Loing ùwagambipogéńdé itọka si..
wikipedia
yo
Jasmine Nwaọ́fíìsì tí a bí ní ọjọ́ kejì Oṣù Kejì ọdún 1995, ó jẹ́ Menbọ́ọ̀lù sàpẹrẹ ti ikọ̀ First Bank BC ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ó sì jẹ́ Menbọ́ọ̀lù sàpẹrẹ tí ikọ̀ Nàìjíríà (Nigerian National Team).ó sojú Ikọ́ Nàìjíríà ní 2019 Women's Afrobasket.Wagner and Syracuse Statistics sourCereine
wikipedia
yo
Katherine Obiang jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Cameroon, agbohùn-sáfẹ́fẹ́ àti olóòtú èto amóhùnmáwòrán..
wikipedia
yo
Lákòókò, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olóòtú ètò amóhùnmáwòrán fún Nigerian Television Authority (NTA) ní Am Express àti Nigeria Info 99.3FM..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe eré, ó sì ń kópa nínu sinimá àgbéléwò..
wikipedia
yo
Ó kópa nínu eré kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ The Women ní ọdún 2017..
wikipedia
yo
O gba ami eye ni ọdun 2017 pẹlu Kate Henshaw ati Obidi.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Chioma àárínajá (ti a bi ni June 29, 1984) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àlájùsáwọn, tó gbá bọ́ọ̀lù náà fún First Bank àti ẹgbẹ́ orílẹ̀-ède Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọmọbìnrin yìí ni a tún mọ̀ sí Elephant Girl.Iṣẹ́ rẹ̀ Lágbàáyé ó kópa nínú Women's Afrobasket tó wáyé ní ọdún 2017.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1984..
wikipedia
yo
Mfọ́n Sunday Udoka (ti a bi ni ọjọ kerin-din-logun, oṣu kẹfa ọdun 1976) jẹ ọmọ orilẹ-ede Naijiria-Amẹrika tẹlẹri agbabọọlu inu agbọ̀n ti o jẹ oluranlowo olukọni fun ẹgbẹ bọọlu inu agbọ̀n ti awọn obinrin ti orilẹ-ede Naijiria, D'Tigress..
wikipedia
yo
Ti a bi ni Portland, Oregon, Udoka pari ile-iwe giga Benson Polytechnic (1994) ní Portland ṣaaju ki o to lọ si Ile-ẹkọ giga DePaul ni Chicago, Illinois lati ọdun 1994 si ọdun 1998..
wikipedia
yo
O jẹ egbon si olukọni ati oṣere NBA tẹlẹ írúwé Udoka.awọn itọka si..
wikipedia
yo
Ifeoma Iàlùfáà AgGrey-fyd (8 June 1980 – 2 June 2015), known to most simply as Iàlùfáà, was a Ghanaian-Nigerian media personality, writer and public speaker.Igbe Aye ati ètò ẹ̀kọ́baba tí ó bí àgGrey-Flynn jẹ́ ọmọ orílẹ̀-ède Ghana nígbà tí ìyá rẹ̀ jé ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí BKO Nàíjíríà, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàíjíríà..
wikipedia
yo
O kẹkọọ gboye ni Fasiti ti o wa ni Ipinle Abia ni orile ede Naijiria ni bi ti o gboye ninu eko lingtistic ati Communication.ise AgGrey-St- ni ti o je igbohunsafefe bere bi Yunifásítìto lori ero amohunmaworan ni odun 2003..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó darapọ̀ mọ́ wọn ní ilé iṣẹ́ ìbaẹnisọ̀rọ̀ Silverbird ní ọdún 2009, ni ó lọ sí ilé iṣẹ́ ti orí Rédíò Rhythm 95.7 FM àti Silverbird Television ní Awka..
wikipedia
yo
Níbẹ̀ ni ó ti ń ṣe sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ lórí rédíò àti àwọn ètò lórí tẹlifísàn tí àwọn bí Rhythm & Soul, Gospel Vibes and E-merge kí ó tó padà lọsí ilé iṣẹ́ Rhythm 93.7 FM ní Port Harcourt..
wikipedia
yo
O jẹ agbenuso ati agbalejo fun eto Miss Niger Delta beauty pageant ni ẹẹmẹta otooto.Iku OloogbeagGrey-fynn losi Abia lati lo ki awon obi re, oju ona Port Harcourt ti o n gba bo ninu oko akero ni awon olosa ti dènà ti won si se sise fun won..
wikipedia
yo
As the Driver was driving, the gunmen opened fire on the vehicle..
wikipedia
yo
AgGrey-fynn was hit by Bullets and died of Kuọlọ́yàyà.Awon miiran pe ọ̀rẹ́kùnrin re ni o n wa oko bọ wásí ile ni ojo keji osu kefa, odun 2015..
wikipedia
yo
Níbi tí ó ti lósì Ábíà láti lọ rí àwọn òbí ati mọ̀lẹ́bí rẹ̀, wọ́n fẹ́ẹ́ dé ibẹ̀ ni àwọn ọlọ́ṣà dá wọn lọ́nà, tí wọ́n sì yin ìbọn nígbà tí ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ gbìyànjú láti wakọ̀..
wikipedia
yo
Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣẹlẹ̀ ní ọwọ́ aago méje ìrọ̀lẹ́ ní agbègbè ilé AgGrey-fynn..
wikipedia
yo
Ìbọn tí àwọn ọlọ́ṣà yín lọ mú kí AgGrey-fyd wà ní agbára ẹ̀jẹ̀, tí wọ́n sì gbé ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àwọn olugbe agbegbe ti isele yii ti sele ni won gbe AgGrey-fynn losi ile iwosan nibi ti won ti pe o ti di àìsí ki o to de ile iwosan.Ẹ wòlĩst of unsolved Murdersáwọn itọkasiExternal linKSIàlùfáà at Rhythm 93.7 FM1980 births2015 Murders in Nigeria2015 Deathṣáṣá State University Alubereonaty pageant hostss by Firearm in rivers StateFemale Murder victimsNigerian Infoọ̀tọ̀ọ̀tọ̀Nigerian People of Ghanaian Descent, Radio Tẹ́weters, Women Radio Anadters, Television Anadters, Women Television Anadters, Women Writers Murdered in Port HarcourtSilverbird Communications People Meàṣers Murrs in Nigeria Against Women in Nigeria..
wikipedia
yo
Sarah Ogoke (ti a bi ni ojo karundinlogbon osu kefa odun 1990) je agba boolu owo omo orile-ede Naijiria ati Amerika fun egbe agbaboolu Ferrovidénú de Maputo ati egbe agbaboolu owo orile-ede Naijiria.O kopa ni ere ijide ti awon elegbe re obinrin ti o waye ni odun 2017 ati 2019..
wikipedia
yo
Ogoke je okan lara awon omo egbe agba boolu owo awon obinrin ti a mo si, D’Tigress nigba ti won kopa ni idije boolu owo World Cup FIBA fun awon obinrin ni odun 2018, idije naa waye ni Tenerife, Canary Islands, Spain.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Linda Ogububu (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kẹrin ọdún 1978) jẹ́ agbá-olùwá sínú agbọ̀n ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ó ń gbá fún ẹgbẹ́ Women's Basketball Center..
wikipedia
yo
Ogubu lo si Fasiti ilu California, ni orile-ede Amerika ode tun gba Booolu pelu the Nigeria Women's National Basketball Team ni 2004 Summer Olympics.ayé re a bi Ogubu sinu idile Carolinewe Chinwe ati John Browndie ni IpinleAnambra, ni orile-ede Naijiria-ede Naijiria ni ojo kejila osu kerin odun 1978.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
O jẹ agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede Senegal, o tun jẹ agbabọọlu lọwọ iwaju fun iko Bayern Munich ninu ìdíje Bundesliga..
wikipedia
yo
O tun gbaju-gbaja ati okan lara awon agbaboolu ti o dara jù lọ ni ilẹ Afrika..
wikipedia
yo
Won mo on fun ere-sísá, ege-gígé lori papa.mane beere ere boolu afẹsẹgba pelu iko egbe agbaboolu Metz ninu idije Ligue 2 ti ilu France nigba ti o si fi je omo odun okan-din-logun..
wikipedia
yo
Sugbon o kuro ninu iko naa ti o si dara po mo iko Red Bull Salzburg ni odun 2012 pelu Milionu merin Euro, eleyii ti o si Ife eye ati kọ́ọ̀pù ese kuku ni odun 2013-14..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà náà, mane lọ sí ikọ̀ agbabọọlu Southampton ti Ilu England pẹlu ọwọ́ tí ó tó 11.8m Euro..
wikipedia
yo
Tí ó sì gba àmì ẹ̀yẹ Fatest HRick ní ìṣẹ́jú àlénà dín lógo rin nínú ìdíje náà, nígbà tí wọ́n ń kojú iko aston Villa.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
MactaBene Amachrẹ̀ẹ́ (ọjọ́ ìbí jẹ́ ọjọ́ tí ó gbẹ̀yìn oṣù Kínní ọdún 1978 ní Ìpínlẹ̀ Port Harcourt ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ agbábọ́ọ̀lù sínú ìwọ̀n fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ìgbà kan rí tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2001, òun yìí ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó sì wá láti orílẹ̀ ède Nàìjíríà láti ṣeré ní WNBA..
wikipedia
yo
Amachrẹ̀ẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n gbá bọ́ọ̀lù tí Nigeria Women's National Basketball Team fún ìdíje olimpiki ìgbà ooru ti 2004..
wikipedia
yo
ó tún jẹ́ ọmọ ọba ti ẹ̀yà ojúka ti ìlú Kalaba ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Àwọn ìkọ̀sílẹ̀1978 Birthsáwọn ènìyàn AlààyèOlympic Basketball Pprs of NigeriaBasketball Pprs at the 2004 Summer Olympic: Christian University Alumníní ExPatriate Basketballte People in the United States Women's Basketball Pprsɔɔtas Women's Basketball Pvterfin From Port Harta Harta Games Gold MeDalists for Niáa Games MeDa MeDalists in Basketballls at the 2003 All-Africa Games (Basketball (Basketball
wikipedia
yo
Ìtọrọ UMOH-Coleman (ọjọ́ ìbí rẹ̀ ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejì ọdún 1977) jẹ́ oní eré ìdárayá ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti agbábọ́ọ̀lù àfọwọ́gbá tẹ́lẹ̀rí fún ẹgbẹ́ WNBA..
wikipedia
yo
Ó gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Cleson Tigers ní ìgbà tí ó wà ní ilé-ìwé, ó sì jẹ́ adarí ẹgbẹ́ náà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2002, Atlantic Coast Conference yan ìtọrọ fún ‘50-50-Year All Star Women's Basketball Team,' àti fún fún '25th anniversary Tournament' Teamigbé ayé ìbéèrè pẹ́pẹ́ a bí ní Washington, D.C., Umo-13 dàgbà ní HephzAFH, Georgia..
wikipedia
yo
Ó lọ sí hephzÌbáh High School, ó sì gba bọ́ọ̀lù afowogba fún ẹgbẹ́ The Lady Rlsls Labẹ Akọni2 Wendell Lofton..
wikipedia
yo
bẹm ogunrọ je agbóhùn safefe ile ise iroyin ati amohunmaworan, olootu fiimu ati araso/amúnidara..
wikipedia
yo
Oun ni oludasile ati oludari ile ise e BooKings Africa, ile ise kan fun pese Kardi fun lilo ero ayelujara ni ilẹ Afrika..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọbíbí Ìpínlẹ̀ Èkìtì ní apá ila-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó ń sọ èdè Gẹ̀ẹ́sì, Èdè Faransé àti èdè Spéìsí.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Articles with Hcardszina Saro-Wiwa (ti a bi ni ọdun 1976, Port Harcourt, Nigeria ) jẹ olorin fidio ati onífíìmù ti o gbé ni Brooklyn..
wikipedia
yo