cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Articles with HcardOnito Olufunmilayo Ewa jẹ adari awọn oniroyin ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
O jẹ Alaga Punch media Foundation, ti awon igbimo Punch Nigeria limited yan ni odun 2018, leyin iku egbon re Gbádébọ̀wale Wayne Aboderin, ni ojo ogbon osu karun-un odun 2018..
wikipedia
yo
Kí wọ́n tó yàn an ìyọpọ̀ gẹ́gẹ́ bí alága, ó ti dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ náà ní ọdún 1994, ó sí ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olùdarí tí kí Í ṣe àṣẹ ilé-iṣẹ́ náà.àwọn ìtọ́pọ̀ àwọn onílọ́rin ara Nàìgbé ènìyàn òkẹrin..
wikipedia
yo
Articles With HcardsTunde Iso (tí a bí ní ọjọ́ 16 Oṣù August, Ọdún 1977) jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, oníéfẹ́ nípa ọ̀rọ̀ àwùjọ, àti olóòtú ìwé-ìròyìn Fínutut..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ PDP to dije dupo Gomina Ipinle Osun ni ọdun 2018..
wikipedia
yo
Eso ni oludasile ẹgbẹ Youthocracy; Aare Fix Nigeria Group ati onkọwe awọn iwe African security solution and vision for Africa.Awon itọkasi awọn oniroyin ara Naijiriàwọn oloselu ara Naijiriawọn Ọjọ́ìbí ni 1977awon eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Articles with Hcard: FIófó (tí a bí ní ọdún 1942), tí a tún mọ̀ sí " Uncle Tam ", jẹ́ ayàwòrán ìtàn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó gbajúgbajà fún àwọn àwo-orin rẹ̀ tí n sọ ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ Nàìjíríà, Fiófó tún jẹ́ òṣèré fíìmù, ònkọ̀wé, aláriwíwí àti Olùdámọ̀ràn lóri Media..
wikipedia
yo
àwọn kókó inú fíìmù rẹ pẹ̀lú àwọn olórin Nàìjíríà Biodun Olaku, J ‘Okhai Oaniàlùfáà àti Olú Amoda ..
wikipedia
yo
Ààfin ọba, ìlú Benin; (Agọ́n, ìlú Beninàwọn ìtọ́kasí àwọn oníròyìn ará Nàìjíríààwọn Ọjọ́ìbí ní 1942àwọn ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Ado Ahmad Gidan DBino, jẹ́ onkọ̀wé èdè Hausa, onkọ̀wé, akéde, oníròyìn, olùṣe fíìmù, olùdarí àti òṣèré fíìmù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó kọ̀wé fún bíi ọgbọ̀n ọdún lórí àwọn àkọlé oríṣiríṣi..
wikipedia
yo
Ó ti gba ami-eye member of the order of the Niger (Mon) ní ọjọ́ kokandinlogbon Oṣù kẹsán-an, ọdún 2014, lati ọwọ́ Aare Goodluck Ebele Jonathan.asas iwe ìtàn àròsọ tí ó tẹ̀ jáde in dá sọ dá kaùná 1&2, àjadèjáde nípasè fìBin dà Publishers FM, Kano..
wikipedia
yo
àti HIPra dáì másọ̀yà 1 & 2, àtẹ̀jáde nípa Gidan DaBin Publishers Kosanyan Zamani 1& 2, àtẹ̀jáde nípa Gidan DaBin Publishers Acv, Kano..
wikipedia
yo
Ọdún 1993 àti ọ̀kan ti ọ̀kan mi (Translation of In dá sọ dà káuna), àtẹ̀jáde nípasẹ̀ Gidan DaBino Publishers nígbà́n, Kano..
wikipedia
yo
Ọdún 1993 wáni hánì ga Allah 1 & 2 jade nipa Gidan DaBin Publishers nígbàmọn, Kano..
wikipedia
yo
Ọdún 1994 àti _ (ìtumọ̀ tí Kosílẹ̀ Zamani), tí a gbejade nípasẹ̀ Gidan DaBinto Publishers nígbà' Kano..
wikipedia
yo
Ọdún 1995 Kaico!, Àtẹ̀jáde nípa Gidan DaBin Publishers nígbà' Kano..
wikipedia
yo
Ọdún 1996 Duniya sai SANnu, atẹjade nipa Gidan DaBin Publishers Marc, Kano..
wikipedia
yo
Ọdún 1997 Malam ZAlimu, (Ere-iṣere Hausa kan tí ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ àmì-ẹ̀yẹ 1st ti 2009 Ṣebíeer Mohammed Bibùsùn káráyé Prize in Hausa Literature), àtẹ̀jáde nipasẹ Gidan DaBin Publishers nígbà, Kano..
wikipedia
yo
Ọdún 2009 dáKíkà TaLatin Atẹjade nipasẹ Gidan DBin Publishers nígbà' Kano..
wikipedia
yo
Ọdún 2014 Ẹ̀bùn Ọ̀la ni Idanimọ awọn akitiyan ati awọn ilowosi to tayọ si igbega Litireso Hausa..
wikipedia
yo
Ọdún 2013 Ṣebíeer Mohammed Bibùsùn káráyé Prize in Hausa Literature (play Category) 2009 Ìtọ́kasí àwọn oníròyìn ará NàìjíríàÀwọn òṣèré fíat Ara Naijiribọ̀wọ̀ Olukọwe Ara Nàìjíríààwọn Eniyan AAlààyè Ọjọ́ìbí ní 1964..
wikipedia
yo
Articles with Hcardsshaìbú túmọ̀líìka (tí a bí ní ọjọ́ 4 Oṣù kejìlá, ọdún 1970 ) jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó tún jẹ́ olórin, alábòójútó àṣà, PRP àti Agbaninímọ̀ràn lórí ẹ̀rọ ayélujára àti Olùtọ́jú fíìmù...
wikipedia
yo
O kẹkọọ gboye ninu ẹkọ Mass Communication ni University of Lagos, o si ti kawe ni Lagos State University School of Communication ati ni University of Lagos nibi ti o ti gba BSc (First Class) ni Mass Communication ati Msc (Distinction) bakan naa..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi “Akọ̀wé ìwé-ìpamọ́ tó ṣe déédé jù lọ” lórí àwọn akọ́lé tí ó jọ mọ́ Nollywood..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, ó ṣatẹ̀jáde ìwé rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Movix, tí ó sọ àwọn ìpele ìgbásókè ti Nollywood..
wikipedia
yo
O jẹ olori Igbimọ ti Awọn oluṣakoso ti ọdun 2017 ni Africa Movie Academy Awards.Awon ibatan ẹgbẹ ijo ti Nigeria (Alaga) Ile-iṣẹ Ijo ti Orilẹ-ede ti Nigeria (ẹgbẹ Aṣaaju-ọna) Federation of International Film Critics (FiPresci) (Akowe Gbogbogbo, ẹgbẹ Naijiria) Federation of African Film Critic, (Akowe Gbogbogbo, ẹgbẹ Naijiria) eto Alakoso alejo Kariaye (Awon ọmọ ile-iwe) The Berlina Talent Campus te (Olùdámọ̀ràn) Igbimọ Aṣayan Oscar Oscaràwọn Ibọ̀wọ̀ Ìtọ́kasí Awọn Ọjọ́ìbí ni 1970àwọn Onirin Ara Nàìjíríà /
wikipedia
yo
Chris Hhidèrò (tí a bí ní ọjọ́ kàndínlógún Oṣù Kẹta Ọdún 1976) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń gbé fíìmù jáde..
wikipedia
yo
Oun ni olori onkowe ati olootu MNET.itan igbesi aye e Hiji kẹkọọ gboye ninu Eko Literature-in-English lati Yunifasiti Ipinle Eko ati ni Yunifasiti ilu Ibadan.O sise gege bii osere o ri-itage, akàròyìn, oniroyin ati olootu iwe-iroyin ati olukọ ni ile-eko giga..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2005, ni ó ti jẹ́ olùkọ́ ní Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó.Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀ Fuji House of Comd - Director, Over 52 episodes, Television Comedy, Since September 2008 Now we are Married – Director, Television Drama, 18 episodes, 2009/2012.
wikipedia
yo
Vip - Director, 15 episodes, Television thriller, 2010 Big ètò, writer-director-producer, short film (12)?”)..
wikipedia
yo
- Head writer/story jíjẹ forbidden - MNET series..
wikipedia
yo
Articles with Hcardsadewale Maja-Pearce (tí a bi ni odun 1953) je onkowe, akoroyin ati LÁMÈYÍ, to gbajugbaja fun awon aroko re..
wikipedia
yo
O ti ko opolopo iwe, bii my father's country ni odun 1987 ati the house my father built ni odun 2014, ati ọpọlọpọ iwe onítàn.Ìbéèrè ayé ati ètò eko re Adewale Maja-PearPearce ni a bi ni ilu Lọndọnu, England, sinu idile kan ti won je omo Geesi ati Yoruba..
wikipedia
yo
Ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó lọ sí ilé-ìwé St..
wikipedia
yo
May Ellen Eustats Mofe-Damijo (1956 - 1996) tí a tún mọ̀ sí mẹ́ẹ̀dọ́ jẹ́ akọ̀ròyìn àti oǹkò, tó ṣacjáde Classique Magazine..
wikipedia
yo
ìwé-ìròyìn náà gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ akọ̀ròyìn bíi délé mọ̣́mọ̀dù, ben Charles Obi, àti Rudolf Okonkwo.Mofe-Damijo tun kọ́ àwọn ìwé díẹ̀ bíi Dream Maker àti Center Spreadad.Àwọn ìwé àkọsílẹ̀ eseese, May Ellen (1989)..
wikipedia
yo
Mosky Makura jẹ́ onkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọ̀ròyìn, òṣèrébìnrin àti onígébìnrin tó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi olùdarí Africa No Filter, èyí èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó ń rí sí àyípadà tó ń bá ilẹ̀ Africa látàrí ẹ̀rọ ayélujára.Ìgbésí ayé wọn bí Makúkú ní Èkó, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìdílé Akisemoyin, èyí tó jẹ́ ìdílé ọba ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ètò ìṣèlú, ètò ọrọ̀-ajé àti ìmọ̀ òfin, láti Yunifásítì ti BuUC..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1998, o ko lọ si South Africa, ati ni ọdun 1999, o bẹrẹ ile-iṣẹ tirẹ..
wikipedia
yo
Oun ni oluṣakoso keji fun Communications Africa ni Bill and Melinda Ggates Foundation..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2017, ó jẹ́ aṣojú ẹgbẹ́ náà ní South Africa.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn oníròyìn ará NàìjíríàMÚ ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Joy Uche Angela rìndi (tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1946) jẹ́ Mínísítà Nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí àti aṣojú Nàìjíríà sí ẹgbẹ́ United Nations ní New York láàrín ọdún 2008 sí 2017..
wikipedia
yo
Oun ni obinrin akọkọ lati jẹ aṣoju si ẹgbẹ United Nations lati orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Kí ó tó di Mínísítà, àìṣéédéé, tí ó jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, jẹ́ adarí àgbà Nigerian Institute of International Affairs (niia).Ààrẹ Olusegun Obasanjo yàn gẹ́gẹ́ bí òkè òkun ní ọjọ́ ọgbọ̀n óta kẹjọ Ọdún 2006.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Reuben Muọkà je olootu ibanisoro fun Vanguard Newspaper nigba kan ri, o si tun fìgbà kan je oludari agba fun Nigeria first Mobile TAon operator, lọwọlọwọ, o je oludari public Affairs fun Nigerian Communications Commission.eto ẹkọ rẹ muọkà kẹkọọ gboye ninu eko ise Tiata ni University of Ilorin..
wikipedia
yo
O si tun lo si University of Lagos lati kẹkọọ nipa Mass Communications, nibi ti o ti fara ṣiṣẹ́ ninu Public Relations ati advertising.ẹgbẹ to dara pọ̀ mo muọkà jẹ ọmọ ẹgbẹ; Nigerian Union of journalist, Nigeria Institute of Public Relations ati Registered Practitioners of advertising.Awon itọkasi awon oniroyin ara Nàìire eniyan Aele..
wikipedia
yo
Òtòṣìrie Obi-Young (tí a bí ní ọdún 1994) jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olóòtú àti akọ̀ròyìn akọ̀ròyìn..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olóòtú àgbà fún Open Country Mag, èyí tó jẹ́ ìwé-ìròyìn tó sọ nípa ilẹ̀ Africa, àti àwo Lítíréṣọ̀ rẹ̀..
wikipedia
yo
O jẹ olootu ti Shuku Nigeria, eyi to je apa kan CNN, tó ń soro nípa iṣẹ́-ọnà orílẹ̀-èdè Naijiria, idokowo rẹ ati ere-idaraya rẹ..
wikipedia
yo
O jẹ igbakeji olootu ti iwe-iroyin ori ero-ayelujara Brittle Paper..
wikipedia
yo
OgechukwukanMawe Okonwo jẹ́ olugbohunsafefe àti olóòtú orí rédíò, tó ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ bíi olóòtú ètò orí Balu FM, lẹ́yìn tó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú RayPower FM..
wikipedia
yo
Ó ti ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olóòtú ètò orí rédíò fún bíi ọdún méjì..
wikipedia
yo
O Belre pelu eto kan to pe ni 'straight from the heart', lori Raypower FM, ni osu kerin, lodun un 2002..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, ó di olóòtú ètò lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán, níbi tí ó ti jẹ́ olóòtú àwo ètò bíi ‘Top 10 Countdown Show’ àti ‘Rock Radioìdámẹ́wàá
wikipedia
yo
Ni osu kejo, odun 2003, o bere ise pelu Bolola 98.9 FM, eyi to wa ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
O ti se olootu awon eto bii 'Whiles of the night', 'The AfAfAf Blazing Drive', 'Top 8 Countdown', ‘The Sunday morning show' ati ‘The Super morning show' lori Uv FM..
wikipedia
yo
O ti gbalejo awọn olokiki elere idaraya bii 2face Idibia, D'Banj, Don Jazzy, Ali Baba, Mike Ezuruonye, Rita Dominic, Olamide, Kenny & D1, Omawumi ati bẹẹ bẹẹ lọ.Awon itọkasi awọn eniyan alààyẹ̀awon oniroyin ara Naijiria..
wikipedia
yo
Articles with HcardsMalcolm Ohanwe (ti wọ́n bí ní ọdún 1993 ní Munich ) jẹ́ akọ̀ròyìn, ara German-Nigerian, gbajúgbajà lórí ẹ̀rọ-ayélujára àti olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán..
wikipedia
yo
Ènìyàn Media àti Agbàlejò TV.Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ Malcolm Óhan tí wọ́n bí ní Munich, ní Germany, ìyá rẹ̀ jẹ́ ará Palestine, nígbà tí baba rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O bẹrẹ iṣẹ rẹ gege bii akoroyin leyin to kẹkọọ gboye ni ile-iwe girama, gege bi onkọwe fun German Television Network prosieben, ati bii olootu ile-iṣẹ German kan, ti orukọ wọn lori ẹrọ-ayelujara n jẹ Rap2]de.O.O kẹkọọ nipa ede Gẹẹsi, Middle Eastern Studies, ati Romance Studies ni Ludwig-imieoans-University, ni Munich..
wikipedia
yo
Chris Maduabchukwu Okolie (tí wọ́n bí ní ọdún 1949, tí ó sì kú ní ọdún 2007) jẹ́ olùpolówó eré orin Nàìjíríà àti Akòtẹjade ìwé tí ó sì tún jẹ́ olùdásílẹ̀ New BReed Organization, àti Agbejade ìwé-ìròyìn New Birán_*Báátara rẹ̀ ọkọ dá bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olùpolówó orin ní àwọn ọdún 1960, tó ń ṣẹgbẹ́ àwo ètò ìjíkàn ní gbọ̀n J.K..
wikipedia
yo
O kẹkọọ nipa ikede funjo diẹ ni Watford College, ni London ki o to pada silẹ Naijiria.Awon itọkasi awọn Ọjọ́ìbí ni 1949awon oniroyin ara NaijiriaÌwo Ojo- ni 2007..
wikipedia
yo
Yusuka Adébọ́lá Ọlani jẹ́ akọ̀ròyìn, agbẹjọ́rò àti alábòójútó, tó ń ṣiṣẹ́ bíi olùdámọ̀ràn pàtàkì lórí Media àti ìpolówó sí Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ilẹ̀ Nàìjíríà, Bùkọ́lá Sàràkí.Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ Yusuph Ọláníyọnu ni wọ́n bí sí ìlú Èkó ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù keje, ọdún 1966..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Ògùn State Polytechnic, Abeokuta (èyí tí a mọ̀ sí Moshood Abiola Polytechnic báyìí) láàrin ọdún 1983 sí 1988, ó sì jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ tó dára jù lọ láti ẹ̀ka ẹ̀kọ́ Mass Communication.Àwọn ìtọ́kasí àwọn oníròyìn ará Nàìjíríààwọn ènìyàn Aàyéàwọn Ọjọ́ìbí ní 1966..
wikipedia
yo
OyeDapo Oyèkúnlé "Dapo" OlorunYomi (ti won bi ni ojo kejo osu Kọkànlá odun 1957), je akoroyin omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Òun ni Olóòtú àgbà fún ìwé-ìròyìn Premiun Times èyí tí ń ṣe ìwé-ìròyìn ti ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Òun kan náà ni olùṣàkóso àgbà fún Premium Times fún investimóoru Journalism (PTbb)..
wikipedia
yo
Òun ni olùdarí fún Economic and Financial Crimes Commissin (EFCEC). Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ International ríran of the Year Award (1995) Pen Center (West) Freedom tó Write Award (1996) Press Freedom Award of the National Association of Black Journalists (NAB)New York U.S.A (1996) Hellman Hemett Grant of the Human Rights Watch (1996) Diamond Award for Media Excellence's Lifetime Achievement Award by Diamond Publications (2017) CP International Press Freedom Awards (2021)Àwọn Ìtọ́kasí àwọn oníròyìn ará ará Nàìjíríà Ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1957..
wikipedia
yo
Articles with HcardsVictor akọ́ládé Olowu (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 8, Oṣù October, Ọdún 1992) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi agbóhùnsáfẹ́fẹ́ àti oníṣòwò orí ẹ̀rọ ayélujára, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Kolade, Mr dominate.Ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ Oṣù Kẹwàá, Ọdún 1992 ní ìlú Ijẹ̀bú, Ìpínlẹ̀ Ògùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O lo si Ile-iwe Mayflower School, ni ìkẹ́nnẹ́ fun ile-iwe girama re, o si te siwaju si lati kẹkọọ ninu igbẹ-iwadii-jade ni Federal Radio Corporation of Nigeria.Awon itọkasi awọn olorin ara Naijirimeje oniroyin ara Naijirimeje Ọjọ́ìbí ni 1992awon eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Articles with short Desshort Description is different from Wikidaeolọjọ́ with HcardsRotimi Alakija (ti a bi ni ojo kerin-din-logun oṣu ọrọ ọdun 1980), ti opo mo si DJ XJájakini, o jẹ ‘ jockey Nàjíríà, Fils igbasilẹ orin ati olorin alágbàsile.ibẹrẹ aye England ni a ti bi Rotimi Alakija si owo awon obi Naijiria..
wikipedia
yo
Ni ọdọmọde, o pada si Naijiria lati lepa Eko ni ile Eko King's College, ilu Eko..
wikipedia
yo
Rotimi Alakija padà sí UK láti kọ́ ẹ̀kọ́ physics àti ìmọ̀ sáyẹ́nsì kọ̀pútà ní Yunifásítì Il, ní bí tí ó ti gba oyè ẹ̀kọ́ ilé-ìwé gíga..
wikipedia
yo
O tun pada ko eko isuna owo Kọmputa ni Yunifasiti Brunel, London.Iṣẹ DJ Xgono bẹrẹ iṣẹ ojogbon September jockey ni odun 2003 nipa opo ise sise ni ebun ile ijo ale, pelu AURA MayFair, Penthouse, Funta Buddha ati jalouse..
wikipedia
yo
Laarin awon odun ise re, DJ Xdraising ti ba orisirisi awon osere bi Ne-yo, Rihanna, Mario Winans, Brick and Anack, Nas ati fat Joe sise po.Ni abala ti odun 2010 ti Nigeria Entertainment Awards, ti o waye ni United States, DJ XAnaAna gba ami eye DJ ti o dáraju ni aye..
wikipedia
yo
a yàn láti díje DJ tí ó dárajù ni atuṣe ti ọdun 2011 ti Beffta Awards..
wikipedia
yo
O tun ṣe fííhan ni House Party Big Brother ọdun 2013.Ni ọdun 2011, DJ Xgono di DJ ilẹ̀ ilẹ̀ fun Coolfm 96.9 O si darapọ mọ Empire Mates Entertainment gẹgẹbi oṣiṣẹ DJ ti Wizkid...
wikipedia
yo
DJ Xtso ṣe ìgbéjáde orin kan “i'm XAnavi" ti olorin ti UK-Naijiria mo EA.Ìgbésí Ayé Ara DJ Xọpẹ́– fẹ́ Tinúke Ogundẹ̀rọ̀ ní ọdún 2015..
wikipedia
yo
Otun je aburo si Olowo Naijiria fokesho Alakija.Awon iseawo kan "Poloolo (pelu timaya) "Ibebe" (pelu Olamide) (2013) "Galka Badpelu Dpelu D'Prince and Wizkid) (2014) "Jẹ́jẹ́ (pelu Wizkid (2014) "Siyege" (pelu Terry G) (2014) "Toñight" (peluBanky W and Niyola) (2014) "Shasha" (pelu Kcee and Patoranking) (2014) "Dami si (pelu Lil Ke Ke CDq) (2015) “Oyòyò" (pelu Burna Boy) (2016) “W-Wale (pelu Masterls) (2016) “Pse (pelu Tiwa Savage (2017) gbọ́mọ (pelu Zpelu ibiletan ibile) “2019 O" (2020) “Gaga” (pelu 10–Classic) (2020) “Sweet 16" (pẹ̀lú soft (2020) “pariwo) (pelu D. Àwòrán fidio ↑ akopọ | Awo orin Empire Mates State of Mind (2012) According to x (2015)Wo eleyi naa Àkójọ Òfinjumọ Itaaa[12 ìta Pẹlupẹlu Awo Awo lákòókò Itan xTgaines ede Yoruba Afroàwọn DJ Yoruba hop Yoruba alààyè / Lagos 1990, Lagos Aluhan Yoruba ìrandíran Mo Olorir DJ of the University of rea ijade ni of Brun on lon Family-FM Family- Mo ronú Ọjọ́ìbís ni 1980 ni iran Naijiria..
wikipedia
yo
Florence Séríkí MFR (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndíndínlógún Oṣù Kẹjọ Ọdún 1963 tí ó sì fi àyè sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹta Oṣù Kẹta ọdún 2017) jẹ́ olùdásílẹ̀ àti adarí ilé-iṣẹ́ OmateK Ventures PLC., ilé-iṣẹ́ Nàìjíríà àkọ́kọ́ ní Afrika láti ṣe ẹ̀rọ kọ̀ǹpútà àti àwọn ẹ̀yà ara kọ̀ǹpútà.Ìpilẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Seris ní Ìpínlẹ̀ Èkó ṣùgbọ́n bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Delta..
wikipedia
yo
O lo ile-iwe sekondiri ni Reagan Memorial Baptist Secondary School, sábó, Yaba laarin ọdún 1975 ati 1980 o si tẹ ẹkọ rẹ siwaju ni Federal School of Science, Eko..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Kóglórs of Science ní Yunifásítì Ilé-Ifẹ̀(ti àwọn ènìyàn wá padà mọ́ sí Yunifásítì Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, Ilé-Ifẹ̀). Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
ó jẹ́ ẹni tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ yẹ́ sí ní apá àríwá Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ ma ń fi ṣe apejuwe bi obinrin ṣe le je Akowe ti yo si wa laaye ara rẹ ni Islam, awon miran tun ròó pe o wa lara awon to koko bere jija fun eto ọmọbinrin ni ilẹ Afrika.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Jordan Terrell Carter(a bí ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn-án ọdún 1996) tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ́ sí Robob Carti, jẹ́ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti Atlanta, Georgia.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Halle (orúkọ àbísọ rẹ̀ ni Halle Grace I;du; a bi ní ọjọ́ kẹtàdínlógún Oṣù kejìlá) jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin, àti oníjó ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ń ṣiṣẹ́ fún N3rd Records.Iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 2008, ó ṣeré fún ìgbà àkọ́kọ́ nínu fíìmù Wedless (2008-2009), Wọ́n padà ṣe àgbéjáde fíìmù náà ní BFI London Film Festival ní ọdún 2010..
wikipedia
yo
Eyi ni fiimu akọkọ ti o ti ṣere; awọn oṣere ti o tun wa ninu fiimu naa ni Gideon Okeke, Nneka Egbúná, Jimmy Jean-Louis ati Tope Oshin Ogun.Ki o to di òṣèrébìnrin, Halle, ma ń jó, o ti jo ni ọpọlọpọ idije ijó, o si jawe olubori ni awọn idije bi idije Channel o Dance Africa, ati The Last Female standing ni Maltíná Dance Hall (ọdun 2008)..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, ó ṣe àgbéjáde orin àkọ́kọ́ rẹ̀, Falling in Love, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì gba ti orin náà.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Gabriel AkinBolarin Akinyíyí (a bi ni ojo karun osu kejila, odun 1949) o se igbeyawo pelu Iyaafin Stella A Akinyí ni nǹkan bi odun merinlelogbon seyin ni odun 1956-1961, o lo si ile iwe St John's ti Anglican oke Igbo leyin na, o pada lo si ile iwe local authority Modern oke Igbo, ni odun 1962-1964..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ná, ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ikẹkọ Dicecesan, Wṣàṣà Zaria © Ní ọdún 1975-1976..
wikipedia
yo
ó jẹ́ bishop ti àkọ́kọ́ ní agbègbè Anglican tì Òndó ni ìjọ ti arélé èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2019..
wikipedia
yo
O pari ni 1955el College ti Theology, Ibadan ni 1978 , o jade ni 1981, o je díákónì ni odun kanna ati pe o se ehonu ni 1982, o tesiwaju ninu ise eko re si oak Hill College, ni ilu awon alawo funfun ni odun 1987–1990, nibiti o ti se..
wikipedia
yo
Ní Dhe, bá ó sì lọ sí King's College London láàrin 1999-1991 níbití ó ti gba ọ̀gá ní Èkó nípa ẹ̀sìn ó ti sin ní ọ̀pọ̀ ṣọ́ọ̀ṣì tó wà ní apá àríwá Nàìjíríà, ìko àwọn ibi bẹ́ẹ̀ ní Zaria, Kaduna, Kano, Gusau, Offa àti àkókò báyìí.Àwọn ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Monica Friday (tí a bí ní ọjọ́ ọ̀kan-din-logun Oṣù kẹrin, Ọdún 1988) jẹ́ òṣèré fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà, Oni-ipa, Realtor, Model àti olùdarí ètò.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀a bí Monica ní Badagry ó sì dàgbà ní Ajegunle, àdúgbò tí ó wà ní ìlú Èkó sínú ilẹ̀ onígbàgbọ́..
wikipedia
yo
Ó parí ilé-ìwé girama ní ilé-ìwé gíga (Newland Senior Secondary), Èkó kọ́ tó di pé ó lọ sí Yunifásitì Olabisi Onabanjo, ní Ìpínlẹ̀ Ògùn níbi tó ti kàwé 'Mass Communication'.Iṣẹ́ rẹ̀Ó ṣe ìfarahàn tẹlifísàn àkọ́kọ́ rẹ̀ tí ó ṣe ipa bí àfikún nínú iṣẹ́ àkànṣe wálé Adénúga tí àkọ́lé rẹ̀ ní ‘New Song', ipa fíìmù àkọ́kọ́ gbòógì rẹ̀ jẹ́ ní ọdún 2015 nígbà tí ó farahàn ní fíìmù rẹmi Vaughan-Richards ‘Spoyen'.Monica ti ṣe ìfarahàn ní jara M-Net tí ó gún-gún ọdún 2015, “Do Good” àti fiimu talẹ̀ Africa “Réwa rẹ̀ tú sílẹ̀ sílẹ̀ ní ọdún 2016..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó farahàn nínú fíìmù “Epe" bi Rexìhà.jara tẹlifíṣàn Redo Good The Village Headmaster rẹ̀tẹnumọ́ Mates Wrong, So Goodàwọn Fisan rẹ̀Bad Generation (2008)Being Mrs Elliot (2014)The King's Cross (2019)October 1 (2014)Murder at Prime Suites (2013)The First Lady (2015)Wives On Strike (2014) (2014:2015) N (2019) Mothers & sùúrù In-Law (2019) Timeless Passion (2020) Spoyen) Room Room (2017) Iquo's Journal (2015) (2016) Hoodrush (2012) Brides and a Baby (2011) Bonny & Clara (2019) Saabẹ/2015) My Body My proud (2020) Silent Murder (2021)Àwọn Ìṣẹ̀dáṣe Gralaled (2018)Yorùbá Demons (2018) Best Leori (2019) Romanus (2020) Chronicles of Ejiro (2020)Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Joshua Olufemi (ti won bi ni ojo 22 osu keje, odun 1983) je oṣiṣẹ ori ẹrọ-ayelujara ọmọ orilẹ-ede Naijiria ati oludasile imọ-ẹrọ fun awọn ara ilu..
wikipedia
yo
Òun ni olùdásílẹ̀ dáTuntungbogbo, òun sì ni olùdarí ètò Premiún Times Cntre for investimóoru Journalism (èyí tí wọ́n ń pè báyìí ní The Centre for Journalism Innovation and Development - Cjid)..
wikipedia
yo