cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Olufemi ni akoroyin to tun je asoju Premium Times ni International Consortium of investi5BFR Journalle (Ici) fun Ile-iṣẹ atẹ̀wéjáde Panama Papers ati Paradise Papers.eto Eko ati ise Olufemi kẹkọọ gboye Bachelor's Degree ninu ẹkọ Economics lati ile iwe giga Olabisi Onabanjo ni ọdun 2005 ati oye Master's degree ninu Eko measurement and Evaluation lati ile-iwe giga University of Lagos ni ọdun 2013, ko to lo si said Business School ti University of Oxford, nibi ti o ti gba oye ninu Eko Global Financial Technology..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Institute of Chartered Seindalsts of Nigeria.Àwọn ìtọ́kasí ̀yìn oníròyìn ara Nàìire Ọjọ́ìbí ní 1983 Ènìyàn Alààyè Aàwọ̀..
wikipedia
yo
Sam OmatSeye jẹ́ akéwì, onkọ̀wé ìtàn àròsọ, akotan fún eré Oè-ìtàgé àti akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n bi Sam ní ọjọ́ 15 oṣù June, ọdún 1961, ìpínlẹ̀ Delta, Nigeria ni ó sì ti wà..
wikipedia
yo
O gba ami-eye ti odun 2019 fun National Unsevity Order of Merit (npọM).eto Eko Sám OmatSeye lo si Ile-ẹkọ girama ti Government College, Ughellilli, (Ipinle Bendel tẹlẹ), Ipinle Delta lati ọdun 1973 si 1979 fun eto ẹkọ girama rẹ, o si gba iwe-ẹri Ile-iwe West African School..
wikipedia
yo
O lọ si Federal School of Arts and Science, Victoria Island, Lagos fun eto ẹkọ giga rẹ..
wikipedia
yo
Ó kọ́ ẹ̀kọ́ nípa ìmọ̀ History ní University of Ifẹ̀ (tó ti di Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University) láti ọdún 1980 sí 1985, ó sì gba Bachelor of Arts degree.Iṣẹ́ rẹ̀ ó kọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Lítíréṣọ̀ ní Aminú Kano Commercial College, Kano nígbà tó ń ṣe NYSC láti ọdún 1985 sí 1986..
wikipedia
yo
Láti ọdún 1987 sí 1988 ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ajábó-olùṣèwádìí ní Newswatch Magazine, ó sì ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ nínú ọ̀rọ̀ ilẹ̀ àjèjì àti àṣà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1988, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi òǹkọ̀wé fún African Concord Magazine, ó sì ṣagbátẹrù oriṣiriṣi ìtàn, tó ṣe Àkọsílẹ̀ ìtàn Ibrahim Babangida..
wikipedia
yo
O di igbakeji olootu oselu ti awon iwe-iroyin Concord ni odun 1989.Awon iwe re iwe Kehkere in Wch, Journalism as National Narrative a Chronicle fortold.Awon aramada Croco girl my name is Okoroawon ewi Mandela's Bnes and other Poems Dear baby Ramatu Lion wind and other Poems sCented Offalàwọn ere to kopa ninu The Siege to Mark Professor Wole Soyinka's 80th Birthday awon itọkasi awon eniyan apapoawon Ọjọ́ìbí ni 1961 ara Naijiria..
wikipedia
yo
Sa'A Ibrahim jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti òṣìṣẹ́ ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Oun ni obinrin akọkọ to maa di Alaga Broadcasting Organisation of Nigeria (BO)..
wikipedia
yo
Oun si ni oludari agba fun ero-amóhùn máwòrán ti Abubakar rímí.Ìgbésí ayé rẹ̀ Haji sa'a Ibrahim ni wọ́n bí sínú ìdílé Malam Ibrahim àti Yalwa Bello ni ọjọ́ kejidinlogun osù kẹrin ọdún 1960 ní Légashi Quarters ni Ìjọba Ìbílẹ̀ Gwale ní Ìpínlẹ̀ Kano .Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1960àwọn ènìyàn alààyèàwọn oníròyìn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Nneka Lucía Egbúná (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógun Oṣù kejìlá Ọdún 1980) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrin àti òṣèré bìnrin..
wikipedia
yo
O ma n kọrin ni, ede geesi, Igbo ati ede Pidgin Naijiria.Ìpìlẹ̀ rẹ a bí Nneka Lúcia Egbúná ni Warri, Ipinle Delta, Naijiria, a si to dagba ni ìlú kan naa, iya re je omo orile ede Jemani, baba re si je omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Nígbà tí Nneka jẹ́ ọmọ ọdún meji, ìyá rẹ̀ fi bàbá rẹ̀ sílẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí bàbá rẹ̀ fẹ́ ìyàwó míràn, ìyàwó tuntun yìí fi ìyá jẹ àwọn ọmọ ìyàwó àkọ́kọ́, pàápàá jùlọ àwọn ọmọ méjì tí ó jẹ́ òwòwòtò àti ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin, Anatomi.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Articles with HcardsGbenga Omotoso (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 11 Oṣù November, Ọdún 1961) jẹ́ akọ̀ròyìn àti òǹkọ̀wé..
wikipedia
yo
Òun ni olóòtú ìwé-ilroyin the Nation titi ti won fi yan an sipo Commissioner to ni se pelu Lagos State Ministry of Information and strategy..
wikipedia
yo
Gomina ipinle Eko, iyen Babajide Sanwo-Olu mu sebura lati wo ise ni odun 2019.igbesi aye ati eto eko re ojo Kọkànlá osu Kọkànlá odun 1961 ni won bi Omotoso..
wikipedia
yo
Ó wá láti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, tó wà ní apá gúúsù mọ́ ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O kẹkọọ gboye B.A ninu imọ ede Gẹẹsi ati Litireso ni University of Benin (Nigeria) ni ọdun 1984..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú láti gboyè Masters nínú ẹ̀kọ́ Public and International Affairs ní University of Lagos, akọ́kà, tí ó parí ní ọdún 2007.Iṣẹ́ rẹ̀ Omotoso ti lo ọdún márùndínlógójì nínú iṣẹ́ ìròyìn..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi akẹ́kọ̀ọ́ tó ń kọ́ nípa iṣẹ́ olóòtú ní ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn The Guardian..
wikipedia
yo
Ó padà di igbákejì olóòtú ti Guardian Express, níbi tí ó ti di olóòtú Saturday Guardian..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1999, ní ìbéèrè ìwé-ìròyìn Comet, wọ́n yàn án sípò aṣáájú-ọ̀nà olóòtú ìwé ìròyìn.Ní ọdún 2006, ó tún di olóòtú aṣáájú-ọ̀nà tí ìwé-ìròyìn The Nation..
wikipedia
yo
Ó ti ṣètọ́jú ìwé kan “Àkọsílẹ̀ olóòtú” ní The Nation, níbi tí ó ti kọ̀wé lórí àwọn ọ̀ràn inú ìlú, látàrí lílo ọ̀nà àwàdà láti fi ṣàfihàn àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ náà..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ Nigeria Guild of Editors (ńgé) ati Nigeria Union of journalist (nuj).O jẹ olùfẹ́ ere-idaraya lọpọlọpọ, paapaa ju lọ bọọlu afowogba..
wikipedia
yo
O ti ni lati fi ẹbun rẹ han nibi iṣafihan kan to ti ba bọọlu naa pẹlu akosemose agbabọọlu to wa ni ipo ogun lágbàáyé, ti orukọ rẹ n jẹ aruna okopé, ti o si ṣe daadaa.Àtòjọ ami-eye rẹ Omotoso ti gba ọpọlọpọ ami-eye fun iṣẹ tita rẹ ninu iṣẹ iroyin..
wikipedia
yo
Diẹ ninu awọn ami-ẹyẹ naa ni; ami-eye ti Dame ni odun 2010, ami-eye ti Nigeria Media fun Olóòtú to dara ju lo ni odun 2013, ami-eye Nigeria Media Merit fun olootu to dara ju lo ni odun 2015, ati ami-eye Nigeria Media Merit fun olootu to dara ju lo ni odun 2017.Awon itọkasi awon oniroyin ara Nàìnsi eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1961..
wikipedia
yo
Articles With Hcardschi OyOmah (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ 10 Oṣù April, Ọdún 1966) jẹ́ akọ̀ròyìn, ònkọ̀wé àti AJÀJÀJÀ Ọmọnìyàn..
wikipedia
yo
Ó ti ṣiṣẹ́ fún bíi ogún ọdún gẹ́gẹ́ bíi akọ̀ròyìn, oǹkọ̀wé, OJÀlẹ́sẹ̀ Ọmọnìyàn àti oníṣẹ́ ìròyìn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ghana, Canada, India, orílẹ̀ èdè America, Caribbean àti Europe..
wikipedia
yo
O kẹkọọ gboye PhD ninu Eko Communication and Journalism lati Autonomous University of Barcelona, ni Uab, Orilẹ-ede Spain..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ to n ri si eto aabo ni orile-ede Naijiria ni o mu ti wo si ti i mole nigba ti o wa ni paapa ọkọ ofurufu ti Abuja, bi o se n ti Spain bọ nitori o wo ewu ti won ko "We are all biAFrans" si.eto eko re Oroko kẹkọọ gboye ni University of Calabar, to wa ni Ipinle Cross River, ni orile-ede Naijiria, o si gba M.A ninu eko ise iroyin lati University of Western Ontario, ni London, Ontario, Canada..
wikipedia
yo
O tun gba PhD kan ninu ẹkọ ibaraẹnisọrọ ati iṣẹ iroyin lati Autonomous University of Barcelona, UAB, Spain.iṣẹ rẹ Omah sise, o si kọwe fun ọpọlọpọ ile-iṣẹ iroyin ni orile-ede Naijiria bii; iwe-iroyin Sentinel, Guardian, am News, pm News, The News/Tempo, Concord, Punch ati THISDAY Newspaper, ki oh to lọ si Accra, ni orilẹ-ede Ghana, ni ọdun 1996..
wikipedia
yo
And Banda, f.). Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1966àwọn oníròyìn ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Tobore Ovuoríẹ̀ jẹ́ akọ̀ròyìn, olóòtú ọ̀rọ̀ ìlera àti olùṣèwádìí àgbà pẹ̀lú Premium Times.Ìgbésí ayé Ovu)". ṣe àtẹ̀jáde ìwé àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún..
wikipedia
yo
O bẹrẹ iwadii abele kan ti akole re jẹ Inside Nigeria's Ruthless Human Trafficking Mafia ni ọdun 2013, eyi ti Premium Times gbe jade ni ọdun 2014.Untte bẹrẹ $5,000,000,000 (eyi to n lo bii nmillion) lati owo ile-iṣẹ EbonyLife fun ÌTẸ̀JÁDE fiimu kan ti akole rè n jẹ Oloture láìgbé oríyìn fun un..
wikipedia
yo
O sọ pe fiimu naa jẹ afihan iriri rẹ ninu Inside Nigeria's Ruthless human Trafficking Mafia..
wikipedia
yo
Ẹni tó ni ilé-iṣẹ́ náà, ìyẹn Mo Abudu sọ pé iṣẹ́ ìtàn àròsọ ni fíìmù náà, àti pé oríṣiríṣi ìṣẹ̀lẹ̀ òtítọ́ ló mú lóríyá..
wikipedia
yo
Àlàyé náà tún ní àfikún pé fíìmù ọlọ́ture náà wáyé látàrí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú ọ̀pọ̀ àwọn ilé-iṣẹ́ pẹ̀lú àkọsílẹ̀ oríṣiríṣi lórí gbígbé ènìyàn káàkiri àti ìbálòpọ̀ afipámúni.Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ ọmọbìnrin náà ti gba àmì-ẹ̀yẹ Deutsche Welle (gbọ́kànv) ti Oduhn 2021, èyí tó jẹ́ Freedom of Speech Award.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn ÀAlààyèàwọn Oniroyin ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Articles with HcardSAisha Salaudeen (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù September, ọdún 1994) jẹ́ gbajúgbajà akọ̀ròyìn, ajafun ètò obìnrin, Àgbéjáde ìròyìn ìròyìn àti ònkọ̀wé tó ń ṣiṣẹ́ ní CNN.. Lọ́wọ́lọ́wọ́
wikipedia
yo
Ní Oṣù kọkànlá Ọdún 2020, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Future Awards Africa Prize fún iṣẹ́ rẹ̀ nínú ijabọ ìròyìn, àti bí ó ṣe máa ń kọ ìtàn nípa ilẹ̀ Áfríkà..
wikipedia
yo
Wọ́n pè é láti sọ̀rọ̀ ní Ake Arts and Book Festival ní dun 2020.àwọn iṣẹ́ rẹ̀ tó gboogi single women cannot ẹgbẹ̀rin Property in Nigeria (2019) for Stears Nigeria.
wikipedia
yo
This 9-year-old has built more than 30 Mobile Games (2019) for CNN.
wikipedia
yo
The woman risking her life to Photograph the forgotten victims of War (2019) for CNN.Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1994àwọn Oniroyin ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
ReDmed Christian Church of God ( CCcg ) jẹ́ ìjọ pẹ́ńtíkọ́sítì nlá kan ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.ch Adeboye ti jẹ́ alábòójútó ìjọ náà láti ọdún 1981..
wikipedia
yo
Ijo naa to wa ni Eko ni awon Olùjọsìn to n lo bii 50,000 ni ọdun 2022.Ìtàn Rev..
wikipedia
yo
Josiah Olufemi Akindayọ̀mi (tí wọ́n bí ní ọdún 1909, tó sì kú ní ọdún 1980) dá Ìjọ CCC sílẹ̀ ní ọdún 1952..
wikipedia
yo
Reverend Akindayọ̀mi yàn Enoch Adeboye gẹ́gẹ́ bíi alábòójútó ìjọ náà..
wikipedia
yo
Adeboye jẹ́ olùkọ́ ìlú MatheDÀN ní University of Lagos, ó sì dara pọ̀ mọ́ ẹJÓ ní ọdún 1973..
wikipedia
yo
Wọ́n kọ́kọ́ gba Adeboye gẹ́gẹ́ bíi ògbufọ̀ láti máa tú àwọn Ìdíwọ̀n Akindayọ̀mi láti èdè Gẹ̀ẹ́sì sí èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bíi olùṣọ́-aguntan láti mójútó ìjọ náà ní ọdún 1975..
wikipedia
yo
Yíyàn tí wọ́n yàn án sípò yìí tẹ̀lé ìfiléh tí AkinDayọ̀ fi lélẹ̀..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1990, ile-iwe fun Eko Bibeli fun Ijo rẹmedmed Christian Church of God jẹ dida silẹ.awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Remedmed Christian Church of God ( CCcg ) jẹ́ ìjọ pẹ́ńtíkọ́sítì nlá kan ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.ch Adeboye ti jẹ́ alábòójútó ìjọ náà láti ọdún 1981..
wikipedia
yo
Ijo naa to wa ni Eko ni awon Olùjọsìn to n lo bii 50,000 ni odun 2022.Ìtàn Rev..
wikipedia
yo
Josiah Olufemi Akindayọ̀mi (ti won bi ni odun 1909, to si ku ni odun 1980) da ijo CCC sile ni ọdun 1952..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1990, ile-iwe fun Eko Bibeli fun Ijo Redeemed Christian Church of God jẹ dida silẹ..
wikipedia
yo
Ìyàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aṣáájú (alábòójútó gbogbogbòò) tí ṣọ́ọ̀sì jẹ́ ìtòlẹ́sẹẹsẹ nípa kíka ìkéde tí AkinDayọ̀ ti di èdìdì lẹ́yìn ikú..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1990, ile-iwe Bibeli ti onigbaràpada ti Ọlọrun jẹ idasilẹ.awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Uzoma Okwuchi osim je osere obinrin ti ile Naijiria ti a mo si Uzor Oosik..
wikipedia
yo
O jade ni ipo karun-un ni akoko Kesan-an ninu Gulder Ultimate Search ti ọdun 2012.igbesi ayéó gba oye ninu eto ọrọ aje (Economics education) lati Yunifasiti Ipinle Abia ni ile Naijiria.Iṣẹ Iṣẹ iṣere Uzor bẹrẹ ni ọdun 2004 nigba ti o se ifihan ninu fiimu 'Shallow Watersìdámẹ́wàá
wikipedia
yo
ní ọdún 2005, ó farahàn nínú jara àgbéyẹ̀wò 'Tintin dey' ti BBC World Service Trust..
wikipedia
yo
Àwọn jara tẹlifísàn 'Do Good' àti Hulóró jẹ́ kí o jẹ olókìkí díẹ̀ síi..
wikipedia
yo
Léhìn náà, ó ti ṣe ìfihàn nínú àwọn fíìmù àti jara tẹlifíṣàn èyí tí ó pẹ̀lú Tinsel, The Maze, Flatmate, Edge of Paradise, Doctors Quarters, láàrín àwọn mìíràn.Uzor Oòsìk díje ó sì jáde ní ipò karùn-ún ní Gulder Ultimate Search ní ọdún 2012..
wikipedia
yo
Pàápàá Bótilẹ̀jẹ́pé ó yọ kúrò lẹ́hìn tí ó ṣòdì sí òfin kan nípa yíyọ kùkùté ìtìjú kúrò ní ẹsẹ̀ rẹ̀ bí ìjìyà fún ìparí ìkẹhìn ní ìpèníjà ìkẹhìn ti àkọlé 'Wave Your Flag'.Àwọn fíìmùṣọ̀kan ọdún 2017 Uzor ni a yàn fún ẹ̀ka àwọn fíìmù City People - òṣèré tí ńbọ̀ tí ó dára jùlọ nínú fíìmù Gẹ̀ẹ́sì kan Uzor Osìgank jáde ní ìkarùn-ún ní wíwà Gulder Ultimate ní ọdún 2012, àkókò yìí wáyé ní Uṣákáṣáká, Oroko àkàrà, ìpínlẹ̀ Akwa Ibom .àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Najite dédé jẹ́ òṣèrébìnrin àti adarí fíìmù ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O je arabinrin Michelle Dede ati Richard Mofe Damijo, awon mẹ́tẹ̀ta je osere.idile re oruko baba Najite ni Ogbeni Brownson Dede, Aṣoju Naijiria tẹlẹri si orile-ede Ethiopia.Àtòjọ awon fiimu ti o ti ṣere MTV ShugaPrince of Savannahmamma Miaheartbeat the MusicalhigHall About Erecan of wormsunbrokenbroken NuAncethe Upside Your Head Show It's Her DayBar Beach Blues Rionao tun le ka Michelle dédé Richard Mofe-Damijoawọn itọkasi..
wikipedia
yo
jíà ZIP yuan (5066521).jpg tigers jẹ́ ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá Japanese kan.ÀKÓKO àwọn Tigers Hans jẹ́ ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá olókìkí olókìkí jùlọ ti Japan àti pé wọ́n ní atẹle ńlá kan.tí ó bá Segun, yóò mú ariwo kan wá sí Japan.Oludari Nièyàn kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Shofu Ogbo ni Alakoso àti pé ó gbajúmọ̀ jù àwọn agbábọ́ọ̀lù.Àwọn àlàyé eré-ìwo jẹ́ pàtàkì ti ẹgbẹ́ yìí...
wikipedia
yo
Angel unigwe (orukọ àbísọ rẹ̀ ní Angel Onyinyechi unigwe; tí a bí ní ọjọ́ kẹta-din-lọ́gbọ̀n Oṣù Kẹfà Ọdún 2005) jẹ́ òṣèré obìnrin ti ilẹ̀ Nàìjíríà, ó jẹ́ Alafìwé, àti Akò tí ó tún ṣe ìfihàn nínú àwọn ìkéde Church olókìkí.isẹ́ Réjaọ́n sí ilé-iṣẹ́ fíìmù nípasẹ̀ ìyá rẹ̀, unigwe bẹ̀rẹ̀ bi òṣèré ọmọdé tí ó ṣe àfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọdún 2015 lẹ́hìn tí ó gba àwọn ipa ní ‘Alison’s Stand,' já agbọ̀n Nàìjíríà olókìkí; àti pé láti ìgbà náà ó ti tẹ̀síwájú láti mú ọ̀kan àwọn òǹwòran fíìmù dùnỌdún
wikipedia
yo
Akọ̀ròyìn unigwe ni oníròyìn Nàìjíríà Ọbaji AkPét.Àwọn yíyan rẹ̀ àti àmì ẹ̀yẹunigwe ti gbádùn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn yíyan àti pé ó ti gba àwọn àmì ẹ̀yẹ lọ́pọ̀lọpọ̀ pẹ̀lú òṣèré ọmọde (Child Actor) ti ọdún 2019 ni Ààmì Ẹ̀yẹ Intellects giant; Ó lọ́lẹ̀ pẹ̀lú àmì ẹ̀yẹ Best Young/Promising Actor ní ọjọ́ kẹtà-din-lọ́gbọ̀n Oṣù Kẹwàá ọdún 2019, ní ẹ̀dà ọdún 2019 ti Africa Movie Academy Awards (AMAA) ); Oṣere Ọmọdé tí ó dára jùlọ nínú fíìmù kan ní àmì ẹ̀yẹ ọdún 2021 ‘Best of Nollywood ‘ (B) fún ipa rẹ̀ nínú ‘strain’. Itọ́ka sí..
wikipedia
yo
Yewande Lawal Simpson jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni o jawe olubori ninu idije Miss Lagos Carnival Pageant ni odun 2012.itan re Yetunde ni omo karun-un ninu omo mefa ti awon obi re bi..
wikipedia
yo
O si padanu iya rẹ ni ọdun 2020.Eko rẹ Lawal's ka eko akobere ati sekondiri re ni orile-ede Nigeria, o si tun tesiwaju lati gba ami-eye Bachelor's degree re ninu imo creative arts ni Yunifasiti Ilu Eko.Iṣẹ re ise Lawal ninu sise fiimu bere ni odun 2009 leyin igba ti o ṣere ninu fiimu Living in Lagos..
wikipedia
yo
Trust Bank Nigeria Limited ( Stbn ), jẹ́ ilé iṣẹ́ tó ń pèsè ètò ìnáwó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó gba ìwé àṣẹ lọ́wọ́ báńkì gbogboogbò ilẹ̀ Nàìjíríà ìyẹn Central Bank of Nigeria, Nigeria àti Olùṣàkóso-ìfowópamọ́ orílẹ̀-èdè orílẹ̀-èdè.
wikipedia
yo
Diamond Bank PLC., J olùpèsè iṣẹ́ ìjiwọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Diamond Bank gba nipasẹ access Bank ni osu kejila odun 2018, osi kede lati pari awon isowo ti apapo ni kikun ni idaji akoko ti odun 2019 ..
wikipedia
yo
Diamond Bank ti Dapo ní kíkún pẹ̀lú access Bank láti kọ́ nkan tuntun làkókò tí ó Tọ́jú orúkọ access Bank pẹ̀lú Ààmì kan tí ó mú ìyáàsí Diamond Bank.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Vfd MicroFinance Bank jẹ banki oni nọmba ni kikun pẹlu olu ni ipinlẹ Eko, Naijiria..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́bí Báǹkì oni nọmba o funni ni awọn iṣẹ ifowopamọ ọfẹ si awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Gbenga Odara ni olori banki naa gẹgẹbi oludari alakoso..
wikipedia
yo
Vfd MicroFinance Bank jẹ́ oniranlọwọ ti ẹgbẹ́ VF Ile-iṣẹ idoko-owo ohun-ini pẹlu Nonso Okpala gẹgẹbi Alakoso .Vbank Vbank (v by Vfd tabi V) jẹ banki foju ati pẹpẹ ti o ni agbara nipasẹ Vfd MicroFinance Bank ati pe o ṣe ifilọlẹ ni Oṣu Kẹta Ọjọ 25, Ọdun 2020..
wikipedia
yo
A ṣẹ̀dà rẹ̀ láti fúnni ní ilé-ìfowópamọ́ orí ayélujára ọfẹ..
wikipedia
yo
Lọwọlọwọ, Vbank ti wo diẹ sii ju 500,000 awọn eniyan ti nṣiṣẹ lọwọ ati awọn iṣowo lori pẹpẹ Ile-ifowopamọ fadaka rẹ kaakiri orilẹ-ede Naijiria.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
jáìz Bank PLC, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Bankìí tí ó ń ṣiṣẹ́ lábé Bankìí Isidù tí kò rọgbọkú lé ìjọba..
wikipedia
yo
O jẹ Bankii akoko fun ìdínwo ni orile-ede Nigeria ti olu iya ile ise won wa ni Abuja, olu ilu Nigeria.Ni December odun 2012, Bankii yii je elétò isuna alábọ́dé ni Nigeria..
wikipedia
yo
Tí wọ́n sì ní káàdì ATM àti ètò Bankìí ayélujára, ìbára-ẹni-sọ̀rọ̀ Alátẹjíṣẹ́.Ìtàn wọn dáa sílẹ̀ ní 2003, gẹ́gẹ́ bí jáìz International Pls..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kọkànlá November 2011, jáìz gba ìwé ẹ̀rí láti ọwọ́ Central Bankii ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹfà January 2012, ilé iṣẹ́ Bankii yí bẹ̀rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ilé iṣẹ́ Aladani jáìz Bank Pls ní óógbò ní Abuja, Kaduna àti Kano..
wikipedia
yo
In 2013, jáìz Bank tan kálẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà, ati laarin awọn ilu kéréje kéréje ilẹ̀ náà.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Govbank, na (na duro fun “ Association Orilẹ-ede ") jẹ oniranlọwọ Ile-ifowopamọ Amẹrika akọkọ ti awọn iṣẹ inawo ti Ilu Ilu CitiGroup ..
wikipedia
yo
Citybank ti a da ni 1812 bi City Bank of New York, ati ki o to di first National City Bank of New York..
wikipedia
yo
O ti ni ipa ninu awọn iṣẹlẹ agbaye pẹlu ikọlu Amẹrika ti Haiti.awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Heritage Bank PLC., tí a tún ń pè ní Heritage Bank, jẹ́ ilé ìfowópamọ́..
wikipedia
yo
O je okan lara awon ile ifowopamo ti gbogbo-gbo ti ile ifowopamo apapo ti Naijiria fi owo si, tii se akoso oro ifowopamo ni Naijiria, pelu ase ìṣísẹ̀, lati se Iise dura eto ifowopamo, eto ifowopamo ti ayelujara, eto ifowopamo onidókòwò ati amojuto nkan ini; olu ile ise won wa ni 292b Ajose Adeogun Street, Victoria Island, Eko, Ipinle Eko, Naijiria.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Stanolónìí Tutc Holdings, tí gbogbo ayé mọ̀ sí Stanolónìí IBM ilé-iṣẹ́ tí ó pèsè ètò owó àti Inọwọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wa ni Walter Carrington Crescent, Victoria Island, Lagos..
wikipedia
yo
Stanolónìí IBM Holdings wà lára Standard Bank Group,iléeṣẹ́ iṣuwo nla tí ó kalẹ̀ sí orílẹ̀-èdè South Africa..
wikipedia
yo
Stanẹ́dàrà Tutc Stockjuwọ́kers limited - providing Stock Brorara Service.
wikipedia
yo