cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
ó jẹ́ ẹlẹ́gbẹ́ ti Institute of Chartered Accountants of Nigeria (ican) àti olukọni ọlá ti Chartered Institute of Bankers of Nigeria (cIbn)..
wikipedia
yo
Ni ojo 24th osu kejo odun 2020, Abiru fi ipo sile ni banki Polaris lati dije du ipo igbimọ aṣofin agba ni Eko East labẹ ipilẹ ẹgbẹ All Progressives Congress.ona iṣe oun ni o je oludari agba Ile ifowopamọ First Bank Nigeria Ltd laarin ọdun 2013 si 2016, o si tun jẹ Komisona fun eto inawo ni Ipinle Eko laarin ọdun 2011 si 2013 labẹ idari Babatunde R..
wikipedia
yo
Fashola (San) gẹ́gẹ́ bí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó.Central Bank of Nigeria (CBN) yan an ní oṣù keje ọdún 2016 gẹ́gẹ́ bí alákóso ẹgbẹ́ kan láti rán ilé ìfowópamọ́ skye Bank nínú ewu tí ó ń báwọn fínra..
wikipedia
yo
Àṣeyọrí ẹgbẹ́ yìí ni ó jẹ́ kí ilé ìfowópamọ́ Polaris wà ní oní .Tokunbo tún ṣiṣẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìgbìmọ̀ pẹ̀lú Airtel Mobile networks limited, (báyìí fbn Quest Merchant Bank limited); fbn Bank Sierra-Leone limited; àti Nigeria Inter-bank settlement system PLC(ọ̀rúndún)..)..
wikipedia
yo
Lakoko ajakaye arun COVID 19, o ti ṣètọrẹ awọn iboju Ìparadà 150,000 si awọn ile-iwe alakọbẹrẹ ni agbegbe rẹ.akọsilẹ Aladani lasiko Abiru Gẹgẹ bi Komisona fun Eto Ìnáwó nipinlẹ Eko, Ipinle naa fi owo 80 billion naira, eleyii ti o gba ami eye MeEA Finance Best Local Curpe Bond Award fun 2012..
wikipedia
yo
O si awọn ijiroro lori owo-ori ni ipinlẹ Eko lẹhin ti iṣṣàwárí ti awọn eniyan ti o gba owo-ori ti o ju 5.5 million ni ọdun 2013..
wikipedia
yo
Ìgbìyànjú rẹ̀ tún yọrí sí àlékún àwọn ìrànwọ́ owó-wiwọle lilo ilé-ilẹ̀ sí ohun tí n6.2bn.Abiru tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ tí Lagos HAM Committee, tí ó wà ní ìtẹ̀síwájú Lagos State Home Ownership Movga scheme (HSH) tí a ṣe láti dínkù ìlà ilẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ náà.wwon yàn án gẹ́gẹ́ bí Sẹ́nétọ̀ tí Lagos East Senatorial District nínú ìdìbò á ọjọ́ karùn-ún December, Ọdún 2020àwọn Ìtọ́kasí ...
wikipedia
yo
Funke Adeṣíyán jẹ́ òṣèrébìnrin, olóṣèlú àti olùrànlọ́wọ́ Aisha Buhari, ìyàwó Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, lórí àwọn ìsẹ̀lẹ̀ àṣà àti àwùjọ.ÌPÌLẸ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀adeyán jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Oyo..
wikipedia
yo
O lo ile-iwe time and tidé International School, Ibadan City Academy, Saint Anne's School, ati Oriwu College Ikorodu fun ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ ati sekondiri rẹ..
wikipedia
yo
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ nínú ìmọ̀ òfin ní Yunifásítì Olabisi Onabanjo..
wikipedia
yo
Adéyán kọ nípa ṣíṣe fíìmù ní ilé-ìwé New York Film Academy.Àwọn Ìtọ́kasí eti kẹtaobìnrin aleayoku Lerùàparòkaki Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Òfin méjìdínláàádọ́ta agbára' (The 48 Laws of Power) (1998) jẹ́ ìwé àpilẹ̀kọ onisiipaya ti onkọ̀wé America, Robert Greene kọ ọdún 1998..
wikipedia
yo
Ìwé yìí jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìwé ti New York Timee tà wàràwàrà, wọ́n ta igba kan lé ní mílíọ̀nù kan ìwé náà lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà; it is popular with prison inmates and celebrities.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Robert Greene (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1959) jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ Amẹrika tí ó kọ ìwé nípa strategy, Power, àti Seduction..
wikipedia
yo
O ti ko oriṣiriṣi iwe ti won ta wàràwàrà káàkiri àgbáyé, lara won ni ofin méjìdínláàádọ́ta agbára, the art of Seduction, The 33 Strategies of War, the 50th Law (with lépa 50 cent), mastery, àti The Laws of Human Nature.Nene fìgbà kan sọ wípé òun kì í tẹ̀lé gbogbo imọ̀ràn tí wọ́n bá gba oun, wípé ẹnikẹ́ni tí ó bá gba oun ní imọ̀ràn lè banújẹ́ lọ́dọ̀ oun."Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Shola Adetical (ti a bi ni odun 1963) je òṣèrébìnrin òṣèrébìnrin òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àpẹrẹ àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ìmohùn máròyìn ní Little Miss Joce Joce Comedy Sketch Show series tí Jocelyn jẹ̀ẹ́ Èsìen ko, òun ni ó ń kó ipa Aun Olu Olube lọ́wọ́ nínú fíìmù CBS; Bob Heys AbiShola..
wikipedia
yo
Igbó biseni Igbo omi tabi Igbo ira ti o Tanzania laarin ilu AhoAda ati apa oke Igbo Oshishi ni agbegbe Niger Delta..
wikipedia
yo
Igbó náà tóbi tó ìwọ̀n kìlómítà 219 ni ìbú àti ọ̀rọ̀ tí ó kún fún ilẹ̀ omi.Àwọn koríko rẹ̀igbó bíseni jẹ́ inú irà tí ó kún fún àwọn igi gẹdú àti àwọn koríko mìíràn tí wọ́n sáábà máa ń gbé lásìkò ẹ̀rùn tí ó sì máa ń kún fún omi roro nígbà òjò..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ igi àgbẹ̀ ati àwọn igi mìíràn tí wọ́n fẹ́ràn omi ni wọ́n wọpọ ninu igbó biseni..
wikipedia
yo
Bákan náà, ọpọlọpọ àwọn kóríko omi bíi OṢÍọ ati àwọn kóríko mìíràn ló kún fọnfọn sí ibẹ̀, pàápàá jùlọ lẹ́bàá igbo náà.Àwọn eranko bíseni kun fun ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹyẹ àti àwọn ẹranko-ọnnìlọ́yàn tí wọ́n ṣọ̀wọ́n.Àwọn ìtọ́kasípọ̀] fí ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
De Forest jẹ́ Igbó kan ní Ìpínlẹ̀ Borno, Ariwa apá ila oorun Naijiria..
wikipedia
yo
Ó wà ní gúùsù apá ìwọ̀ ògún Chad Basin National Park, ó sì tó bí kíkàn ìpàdé láti gúùsù ila-oorun Maiduguri, Olú ìlú Ìpínlẹ̀ Borno Gbogbo Borno
wikipedia
yo
Ilẹ̀ sambisa Forest to kilometer èjì dín ní okòó-lé-ní-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta(518).ilẹ̀ sambisa sambisa Forest wa ní àríwá apá ila-oorun ti ìwọ̀ oòrùn Sudanian Savanna àti ní gúúsù Sahel Savannah àti bí kilometer ọgọ́ta láti gúúsù ìlà-oòrùn Maiduguri, olú-ìlú ìpínlẹ̀ Borno..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ rẹ̀ gba díẹ̀ ninu àwọn ìpínlẹ̀ Borno, Yobe, Gombe, Bauchi, lára ile darazo, Jigawa, ati ara ile àríwá ìpínlẹ̀ Kano..
wikipedia
yo
Ó wà lábẹ́ ìdarí àwọn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Nàìjíríà ti askira/UBA ní apá gúúsù rẹ̀, dámboa ní apá ìwọ̀ oòrùn gúúsù rẹ̀, àti kọ́ńdú òun jèrè ní apá ìwọ̀ oòrùn rẹ̀.Àwọn ènìyàn sọ igbó náà ní sambisa forest nitori pé ìlú kan wà ní ẹgbẹ rẹ ti oruko re je sambisa.Ikọ̀ Boko Haram Igbo sambisa, pàápàá julọ ibi ilẹ̀ àpáta ti o wa ni gkarun lẹgbẹ alaroko Cameroon, jẹ ibi ti àwọn ikọ Boko Haram fi n sele, idaniloju si wa pe ibệ ni wọn ko àwọn ọmọ ti wọn ji ni osu gbe ni osu kerin kẹrin ni ọdun 2015.Ni ọdún 2015, àwọn ọmọ Ológun Naijiria bệrệ si n doju kọ Boko Haram ninu igbó náà, sugbọn wọn rẹ̀wẹ̀sì nigba ti wọn ri pe àwọn ikọ Boko Haram ti gbin àwọn àdá oloro ati pe ati pe awọn ikọ Boko Haram mọ bi ilẹ naa se ju àwọn ọmọ ologun lo ologun lọ..
wikipedia
yo
Pelu pelu gbogbo eyi, ni ojo kejidinlogbon osu kerin odun 2015, awon ibudo Boko Haram merin ni Igbo Dodo ni awon omo ologun gba ti won si tu awon obinrin ti o fẹrẹ to meta sile sugbon awon yii kii se awon omo Chibok ti Boko Haram ji gbe.Awon itọkasi jeografi ile Naijiria..
wikipedia
yo
Jos Plateau jẹ́ ilẹ̀ òkè kan tí ó sún mọ́ àárín orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n fún ilé náà ní orúkọ rẹ̀ nítorí pé ó wà ní ìpínlẹ̀ Plateau, àti nítorí Jọs, olú-ìlú ìpínlẹ̀ Plateau..
wikipedia
yo
Ilẹ̀ òkè náà jẹ́ ilẹ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn pẹ̀lú oríṣi àṣà àti èdè.Ilẹ̀ Jọ Plateau Jóṣ Plateau ní ilẹ̀ tí ó tó 8600 km..
wikipedia
yo
Gígùn rẹ̀ kọjá òkun sì tó kìlómítà kan, òun ni ó tóbi jù nínú àwọn ilé tí ó fi kìlómítà kan tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ kọjá òkun ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Àwọn ọ̀dọ́ bi ọ̀dọ́ Kaduna, Odò góńgóla.Àwọn ènìyàn tí ó ń gbé ibẹ̀ Jos Plateau súnmọ́ ààrin Nàìjíríà, ó sì to àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà ọgọ́ta tí ó ń gbé ní ilẹ̀ Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èdè tí wọ́n ń sọ níbẹ̀ jẹ́ àwọn èdè tí ó jọ mọ́ èdè Chad..
wikipedia
yo
méjì nínú àwọn èdè tí wọ́n n sọ jù níbẹ̀ ní èdè Berom àti Èdè Ngas..
wikipedia
yo
Awon ede miran ni Mwaghavul, PIbùdóh, Ron, afiz, Anaguta, fọ́nku, Awewe, Chol, Kofyar, Kuroko, Miship, Muún ati Monyato.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Articles with HcardsCharles Nkaùkà (tí a bí 12 Okufa 2007) jẹ osere, awoṣe, ati ihuwasi media.igbesi aye ibẹrẹ ati abele a bi Nlẹ́kọ̀ọ́te ni Ipinle Anambra ..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé alábẹ̀rẹ̀ Holy Family fún ètò ẹ̀kọ́ alákọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ àti Christ The King College, Onitsha fún ètò ẹ̀kọ́ girama rẹ̀..
wikipedia
yo
O koju ọpọlọpọ awọn italaya nigbati o dagba.Iṣẹ-ṣiṣe ni 2023, o ti yan fun ami-eye fun olori ile igbimọ aṣofin ti Orilẹ-ede ti Awọn ọmọde ti Orilẹ-ede ati pe o gba Alaga Eko ni Nigeria.Awọn itọkasi awọn eniyan Apeawọn àyọkà alaini ohun-inu Wikiẹgbàá..
wikipedia
yo
Masọjà Josiah Cormza (tí a bí ní Oṣù Kẹwa 5, 1964) jẹ́ òṣèré South Africa kan, akéwì àti akọrin..
wikipedia
yo
O jẹ olokiki julọ fun iṣafihan "nkun MhChetta" ni Jonathan UZalo ti o gba ami-eye..
wikipedia
yo
Articles with Hcardsst ayé wan bi Cormza ni Kwa-thema, ilu kan to wa ni agbegbe South Africa ti Gauteng..
wikipedia
yo
Ife rẹ fun isere bẹrẹ nigbati o jẹ ọmọ ọdun 9 ati pe o gbadun kopa ninu iṣere ati awọn kilasi ere..
wikipedia
yo
Ni ọmọ ọdun 14 o kopa ninu idije ere-idaraya ni ile-iwe rẹ eyiti o bori..
wikipedia
yo
lẹ́yìn tí ó parí ilé ẹ̀kọ́, ó rí iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí awakùsà, ó sì wá parí rẹ̀ ní àsẹ̀yìnwá-àsẹ̀yìnbọ̀ pẹ̀lú àwọn awakùsà mìíràn tí wọ́n lọ́wọ́ nínú ìkọlù ..
wikipedia
yo
lẹ́hìn ìyọkúrò rẹ̀, ó pinnu láti lépa àlá rẹ̀ láti di òṣèré kan àti pé gígi àkọ́kọ́ rẹ̀ jẹ́ ìfihàn nínú eré kan tí a pè ní "MfọThummi" èyí tí Gibson Kente jẹ́ olùdarí.Iṣẹ́ ṣímza bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ bí akéwì òṣì tún dìí àti òṣèré tẹlifísíọ̀nù, akọrin àti àròsọ ìtàn..
wikipedia
yo
bibẹẹkọ, ipa ti o ṣe pataki julọ ni iṣafihan ti Olúwa Ilufin aibikita nkunebomvu "nkunzi" MhChetta lori ifihan tẹlifisiọnu ti a wo julọ ni South Africa Uai ..
wikipedia
yo
Ó tún sì farahàn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn jara TV gẹ́gẹ́bí scandal!, Shreads àti Dreams, Rhythm City, Intersexions, Soakud & Partners, àti ṣíṣe àwọn sẹnti pẹ̀lú sĩtholes..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2016, o gba kikopa ipa akọkọ rẹ ni tẹlifisiọnu ni Teleto kan ti wan pe ni “Ring of lies”
wikipedia
yo
Ni ọdun 2004, o kọ awọn oríkì fun awọn ẹgbẹ bọọlu orilẹ-ede South Africa No gba ti Wawan ṣe figagbaga AFCon ni Tunisia ..
wikipedia
yo
O tun ko ati ṣe awọn oríkì igbega fun redio ibudo ti o tobi julọ ni South Africa UKhozi FM ..
wikipedia
yo
Articles with Hcarngngmo George Leipoẹnú Pieterter (ti a bi ni odun 1930 ni Windhoek, Namibia ) o je eyan South Africa tonse akọrin ere, osere, akewi, Alariwisi iwe-kikọ ati Anoth.Eko ati ise Cosmemo Piterse lo si ile-eko giga ti Cape Town o si ko ni Cape Town titi o fi kuro ni South Africa ni odun 1965..
wikipedia
yo
O ti fi ofin de labẹ ofin awọn apejọ riOtous ti 1962..
wikipedia
yo
Sibẹsibẹ, lẹhin ti o rin ìrìn-ajo lati pade akéde Ilu Lọndọnu rẹ ni ọdun 1979 o ko tun wọle si Amẹrika lori alaye isọdi, ti ẹsun fun jijẹ "Communist ti a fura si"
wikipedia
yo
Ni Ilu Lọndọnu, ni awọn ọdun 1960 nigbamii ati ibẹrẹ 70s, Piterterṣe ṣiṣe fun BBC World Service ni bush House ati fun Ile-iṣẹ transcription, agbari ti o wa labẹ itọsọna Dennis Duer ti gbasilẹ ati gbejade awọn iṣẹ ti awọn onkọwe Afirika ni Yuroopu ati Afirika..
wikipedia
yo
Pàápàá òṣèré lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan, Pieterse han ni The Burning, fíìmù eré kúkúrú ìṣẹ́jú 30 kan ti 1968 tí Stephen Frears ṣe ìtọ́sọ́nà..
wikipedia
yo
Awọn ipa, awọn ifiyesi, ati awọn idii lakoko ti o ni idaduro ojuṣaaju kan pato ti Afirika..
wikipedia
yo
Coxmo Piterse nlo Ife ti awon oro lati ṣẹda oríkì ìrètí ati isọdọtun.”Piterṣe awọnkọ ọhirishihi awọn itan-akọọlẹ ti awọn ere ati awọn oríkì fun jara awọn onkọwe Afirika ti a tẹjade nipasẹ heinemann .awọn iṣẹ ṣàtúnkọ́ mẹwa okan-igbese awọn ere ere ..
wikipedia
yo
Gígé igi láti ṣe pákó, gígé igi lulẹ̀ láti gbin irúgbìn àti gígé igi lulẹ̀ láti fi dánó jẹ́ gbòógì jùlọ nínú àwọn ìdí tí àwọn ènìyàn fi ń gé igi lulẹ̀ ní Nàìjíríà.Láàrin ọdún 2000 sí 2005, Nàìjíríà jẹ́ rilẹ̀-èdè tí ó gé igi lulẹ̀ jùlọ ní àgbáyé, gẹ́gẹ́ bí àjọ The Food and Agriculture Organization ti United Nations (FAO) ṣe sọ.Ní àwọn ọdún 1950s, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé ni wọ́n fi òfin de pé kí ẹnikẹ́ni ma gégi níbẹ̀, ṣùgbọ́n nísinsìnyí wọ́n ti gé ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn igi tí ó wà ní àwọn ilé yìí lulẹ̀, ọ̀kan lára àwọn ìdí tí eléyìí fi ṣẹlẹ̀ ni pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ nkan ni àwọn ènìyàn ń ṣe lónìí tí ó nílò kí wọ́n lo igi.Àwọn ìdí tí wọ́n fi ń gégi lulẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ nkan ni òun fa gígé igi lulẹ̀ ní Nàìjíríà.Iṣẹ́ àgbẹ̀ ilẹ̀ tí àwọn àgbẹ̀ nílò fún gbi gbin nkan ọ̀gbìn ń pòsì nítorí àwọn ọmọ Nàìjíríà ń pọ̀ sí lọ, èyí mú kí àwọn agbe má gé àwọn igi inú igbó lé láti fi àwọn ilé náà ṣe oko..
wikipedia
yo
Àwọn àgbẹ̀ míràn tún fẹ́ràn kí wọ́n ma gbin ọ̀gbìn sí àwọn ilẹ̀ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní ọdọọdúnwíwa epo wíwà epo ti fa kí wọ́n gé ọ̀pọ̀lọpọ̀ igi lulẹ̀ ní Nàìjíríà.Lílo igi dáná bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé Nàìjíríà wà lára àwọn orílẹ̀ èdè tí ó ń ta epo..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ Nàìjíríà sì ń lo igi dáná, pàápàá jùlọ, àwọn tí ó ń dáná níbi ìnáwó, èyí mú kí ọpọlọpọ má gé igi lulẹ̀ láì gbin òmíràn.Ọ̀làjú nítorí pé ọpọlọpọ àwọn eniyan ń kó lọ àwọn ìlú ńlá, ó jẹ́ dandan fún àwọn inú igbó àwọn ìlú yìí láti gé àwọn igi inú igbó wọn kalẹ̀ láti kọ́ ojú ọ̀nà, ilé-ìwé àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Railways, Bridges, Schools, in these parts of the country which are now ìhámọ́ra to the forests areas as trees and vegetations are cut down or Híńdù to achieve these development plans.for instance, most first Generation and second Generation Universities like University of Calabar were highly foalari areas but the need to .. These Schools made way for the destruction of these areas.àwọn ìtọ́kasí jẹografi ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Shalẹ́wà Ashafa (tí a bí ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Keje ọdún 1995) tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí Shally jẹ́ òṣèrébìnrin Nollywood ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ́ fún ipa rẹ̀ nínu eré Àjọ- àti The Razaz Guy.Ìpilẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ Shalẹ́wà Ashafa Asha jẹ́ àbíkẹ́yìn àwọn òbí rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ògùn..
wikipedia
yo
O lo ile-iwe akobere ni Christ the Cornerstone Nursery ati Primary School, gra Ikeja, Eko o si lo ile-iwe sekondiri re ni Ilokoko Model College ni Ipinle Osun..
wikipedia
yo
O gba ami-eye ninu ipolongo ọja ni Yunifasiti ilu Eko.Àtòjọ awon fiimu ti o ti se EVol (2017),There iṣ Something,The Razaz Guy,Blood Covenant.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Niger Delta jẹ ilẹ̀ àti iyẹ̀pẹ̀ tí ó ṣàn láti odò Ọya tí ó sì wà ní Gulf of Guinea ti Atlantic Ocean, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló ń gbé lórí Niger Delta, ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì mọ ibẹ̀ sí Oil Rivers nítorí ibè ni wón ti ń se epo pupa ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ibẹ̀ náà sì jẹ́ ibi tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ epo rọ̀bì.Ilé Niger Delta Niger Delta ní ilẹ̀ tí ó tó , ó sì gbà tó 7.5% gbogbo ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Àwọn Ìpínlẹ̀ tí Ilẹ̀ náà dé ní Bàta, Delta, àti Ìpínlẹ̀ Rivers..
wikipedia
yo
Niger Delta ló pín Bight of Benin àti Bight of Bonny níyà nínú Gulf of Guinea.Àwọn ènìyàn Niger deltáawọn ènìyàn tí ó tó mílíọ̀nù ọ̀kanlélọ́gbọ̀n ni ó gbé ní Niger Delta àwọn ẹ̀yà tí ó wà níbẹ̀ sì tó ogójì, àwọn ẹ̀yà bí Ukwuani, Abua, Bìní, Odu/egbe, olókùn-kiri, Efik, ẹ̀san, Ibibio, Annang, òròn, Ijaw, Igbo, Ísókó, Urhobo, kálábárì, Yorùbá, Okrika, ògoni, Ọgbà-Ẹgbẹ́-Wà, Epie-Esasa àti Obolo, wọ́n sì ń sọ èdè tí ó tó ọ̀tà-dín-nìkan-lé-nígba-250)..
wikipedia
yo
Díẹ̀ nínú àwọn èdè yìí ní èdè Ijaw, Ibibio-Efik, Igboid, olókùn-kiri, Central Delta, Edoid, àti àwọn èdè irú Yorùbá,àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Upper Oura Forest Reserve jẹ́ ibi ipamọ́ ohun àdáyébá ní Ìpínlẹ̀ Rivers, Nàìjíríà tí ó wà ní Òkè Òkè ti Odò Oura, nítòsí abúlé Ikọ́di ní Aho West..
wikipedia
yo
O jẹ iyasọtọ ile olomi ti o se pataki kariaye labẹ Apejọ RamSar ni ọjọ ogbon oṣu Kẹrin ọdun 2008.itọkasi..
wikipedia
yo
Igbo Àárín Cross River ati Niger jẹ́ tí ó wà ní ààrin ìpínlẹ̀ Cross River àti ọ̀dọ́ Niger ní apá gúúsù ìlà oòrùn Nàìjíríà.Bí igbó náà ṣe rí igbó náà tàn dé àwọn ìpínlẹ̀ bí Ábíá, Akwa Ibom, Anambra, Ebonyi, ati ìmọ̀, ilé tí ó gbà sì tó ..
wikipedia
yo
Àdúgbò ibẹ̀ ni omi, ìgbà ẹ̀rùn ibẹ̀ sì jẹ́ láàrin oṣù kejìlá sí oṣù kejì.Wàhálà tí ó buyọ̀ ní àdúgbò igbó náààdúgbò tí igbó náà wà jẹ́ àdúgbò tí ó ti ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ olùgbé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, èyí mú kí wọ́n má gé àwọn igi inú igbó yìí lulẹ̀ fún iṣẹ́ àgbẹ̀, láti kọ́lé síbẹ̀ àti fún àwọn nkan míràn bí kí kọ́ ilé iṣẹ́ fún ṣíṣe epo rọ̀bì ní Port Harcourt..
wikipedia
yo
Awon Igbo si wa ni Ipinle Anambra ati awon ibo miran sugbon awon won gbin awon igi sinu Igbo nitori ki won le ge won lati se pákó.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Regina Chukwu jẹ́ òṣèrébìnrin àti Olùgbéjáde fíìmù ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìpilẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Regina Chukwu ní Ìpínlẹ̀ ní ìpínlẹ̀..
wikipedia
yo
O lo ile-iwe Alimosho Primary and Grammar School ki o to tẹsiwaju ni polytechnic ipinle Eko.Àtòjọ àwọn fiimu ti o ti ṣere Ogunso Ìdárò Akun Ejatomi BriDal Shower encounter two Mothers Family tiesáwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Awujọ Afrika jẹ apapo awon awujo ti o wa lati Afrika, paapaa julo awon ti o wa ni orile ede Amerika lowolowo..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń fi ọ̀rọ̀ náà lọ́wewe àwọn tí ó aláwọ̀ dúdú ní ìwò oòrùn àti ìrin Afrika tí àwọn oyinbo kó kóru ní àárín Centuri kerindinlogun sí ọkàndínlógún, ọ̀pọ̀ àwọn eru yìí ni wọ́n kó lo àwọn orílẹ̀-èdè bí Brazil, Amerika, àti Haiti.. ] mátò ti ìdáwà.. ] ↑ ìdárin ti wọ́n maa pínbí ní àwọn oníka ní gbajú láẹ̀ ní àpéwè tí wọ́n fi ọ̀pọ̀ tí wọ́n fi bí ó máa ní ó kọ́ ní onírin * maa ẹni ní pẹ̀lú olórìwè ìjọ òrìwé àwọn pẹ̀lú wọ́n yẹwè tí wọ́n kọ́ àwọn bí pẹ̀lú ti o tún kan bí pẹ̀lú bí bí pẹ̀lú àwọn ọmọ ja ogun sí orílẹ̀ oguń sí wọ́n àwọn tí wọ́n fi ọ̀rìẹ̀ wé lọ́pọ̀ àwọn tí ó tún ní iwó ní ìdá tí wọ́n maa ń jáwé lórí pẹ̀lú ogun ( ogun * maa ń ja àwọn pẹ̀lú wọ́n kọ́ ní wọ́n maa yẹ ti ń já ọmọ, tí àwọn * fi ní wọ́n ma ń fi ọ̀rìẹ̀ró ti àwọn tí ó tún dín àwọn tí ó tún maa bí ti àwọn aláyẹ àwọn ọmọ pà pà nínú wọ́n sí ọ̀wo àwọn tí wọ́n sí àwọn tí wọ́n ti wọ́n maa yẹ àwọn tí _*pẹ̀lú pẹ̀lú _*ní wọ́n*_
wikipedia
yo
Wọ́n tún lè fi ọ̀rọ̀ náà ṣàpèjúwe àwọn ọmọ àríwá Áfríkà tí wọ́n kìí ṣe aláwọ̀ dúdú ṣùgbọ́n tí wọ́n kó lọ sí àwọn orílẹ̀-èdè míràn.Ní ayé ìsinsìnyí, wọ́n ń fi ọ̀rọ̀ náà ṣàpèjúwe àwọn ènìyàn tí ó kọ láti Áfríkà lọ sí orílẹ̀ èdè míràn..
wikipedia
yo
Nítorí pé ọpọlọpọ àwọn pe ẹ̀yà ati èdè ló wà ní Afrika, oriṣiriṣi ẹ̀yà orin ni wọ́n ń kọ, ọpọlọpọ ẹya ati orile-ede si ni asa orin..
wikipedia
yo
Diẹ ninu awọn orin ni Afrika ni Amaano, Jùjú, Fuji, afrobeat, Highlife, Makossa, Kizomba, ati awọn orin miran..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ awọn elo orin si ni wọn n lo ni Afrika..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ awọn orin Afrika jẹ orin Àtẹnudẹ́nu lati iran kan si omiran..
wikipedia
yo
Orin jẹ́ nkan tí ó ṣe pàtàkì sí àwọn ẹ̀sìn ní Nàìjíríà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀sìn ma ń fi orin pìtàn láti ìran kan sí òmíràn, wọ́n sì ma ń jó sí orin tí wọ́n ń kọ.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Iye awon ede ti won so ni Afrika le ni egberun meji, koda awon miran so wipe o le ni egberun meta..
wikipedia
yo
Nàìjíríà nìkan ní tó èdè onídẹ́,(gẹ́gẹ́ bí Sill Ethngue) ṣe fi lédè, Áfríkà jẹ́ ara àwọn ilé tí oríṣiríṣi àwọn èdè pọ̀ sí jù..
wikipedia
yo
Àwọn èdè kọkàn tun wa ni ilẹ̀ Afrika ti wọ́n jẹ́ èdè tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀yà n sọ..
wikipedia
yo
Àwọn èdè bí Arabic, Somali, Amharic, òròmọ, igbo, Swahili, Hausa, gbogbo, Fatini..
wikipedia
yo
Ààjọ African Union kéde ọdún 2006 gẹ́gẹ́ bi "ọdún àwọn èdè Áfríkà"àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Iye awon olugbe Afrika ni bi ogorun-un odun seyin ti po si pelu opolopo iye, opolopo awon olugbe yii si je odo, ara idi fun eleyii ni pe opolopo awon eniyan ni awon orile ede kokan ni ile Afrika kii dagba koja aadọta odun ..
wikipedia
yo
Iye àwọn olugbe ilẹ Afrika ni odun 2020 to bilionu kan le ni ọọdunrun ,miliọnu ti iye awon olugbe yii si n dagba si pelu 2.5% ni ọdọọdun..
wikipedia
yo
Orilẹ-ede ti o ni awọn olugbe ju ni Naijiria pẹlu olugbe ti o le ni igba miliọnu ni ọdun 2020.Iru awọn olugbe Afrika laarin ọdun 1950 si 2021ad eyi ni ifojuda awọn olugbe Afrika laarin ọdun 1950 si 2021ad bi Aajọ United Nations ṣe fi ledeawọn itọkasi..
wikipedia
yo
Odò Congo River, tí àwọn ènìyàn mọ̀ tẹ́lẹ̀rí sí odò Zaire, ní odò kejì tí ó gùn jùlọ ní ilẹ̀ Áfríkà, odò nílé nìkan ni ó kéré jùlọ..
wikipedia
yo
Òun ni odò tí ó jìn jùlọ ní àgbáyé, jíjìn rẹ̀ tó ìwọ̀n ẹsẹ̀ okòó lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin(720)..
wikipedia
yo
Gígùn odò Congo tó .orúkọọru odò náà, Congo/Kóńgò wá láti odò àwọn ènìyàn Kóńgò tí wọ́n ti fi gúúsù etí odò náà ṣe ilẹ̀ rí..
wikipedia
yo
Ọpọlọpọ mọ awọn ẹya ti o n gbe ibẹ̀ yii si "Enkongo".àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Òun ni agbègbè fún iṣẹ́ àgbẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Mauritania..
wikipedia
yo
ÌGBÀ ỌJỌ́ NI agbègbè CheMama jẹ́ láàrín ọdún Oṣù karùn-ún sí Oṣù kẹ̀sán-án, Ọjọ́ tí ó ń rọ̀ ní agbègbè CheMama Ṣì kéré níye..
wikipedia
yo
Awon olugbe agbegbe naa je awon eya Maures ti o ko lati orile ede Mauribùkún ati awon alawo dudu ti o ko lati awon orile ede lati guusu CheMama..
wikipedia
yo
Nígbà ìjọba akónilẹ́rù, àwọn Maureure ma ń wà láti kọ́ àwọn nkan ìyìrérin ní agbègbè náà..
wikipedia
yo
Ni àwọn ọdún 1980s, agbègbè náà jẹ́ ibi tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwon ìjà ẹ̀yà ti ṣẹlẹ̀, èyí sì mú kí ọpọlọpọ àwọn aláwọ̀ dúdú orílẹ̀ èdè náà kó lọ orílẹ̀-èdè Senegal ní ọdún 1989...
wikipedia
yo