cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ní Oṣù Kìíní Ọdún 2017, ó darí ètò ọdún 2016 ti Glo-CAF Awards òun pẹ̀lú òṣèré ìlú NàìjíríàRichard Mofe Damijo.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Fárọ̀ọ́q Adamu Kpèrògi a bí ní ọdún 1973, ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà, akọ̀wé, (born 1973), Media Scholar(Ọ̀mọ̀wé ìgbóhùngba sáfẹ́fẹ́), Akọ̀ròyìn, Blọ̀gá àti Ajìjàgbaraté..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ àfiròyìn lédè àti aṣétúnṣe ìròyìn ní ọ̀pọ̀ ìwé ìròyìn ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó fi mọ́ Daily Trust, Daily Triumph àti New Nigerian.Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i aṣèwádìí ní ẹ̀ka ìwádìí àti ìbánisọ̀rọ̀ tí Ààrẹ ní ìgbà ìṣèjọba Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́, tí ó sì kọ ṣíṣe ìròyìn àti sísọ ìròyìn ní Ahmadu Bello University àti Kaduna Polytechnic.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ á bí Kpero ní ọdún 1973 ní òkúta, BaruTen ti ń ṣe agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìpínlẹ̀ Kwara, ní Nàìjíríà, ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Bariba (báalọ́tọ̀28) People..
wikipedia
yo
Ó lọ sí Báta University Láàárín1993 àti 1997, ní bi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Mass Communication..
wikipedia
yo
Ó sì ní ìwé ẹ̀rí nínú Communication ìyẹn Master's degreeUniversity of Louisiana at laFayette àti Ph.D..
wikipedia
yo
Ní Georgia State University ní United States ní ọdún 2011.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ọmọ oba Tony Momoh (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹrin ọdún 1939, tó sì kú ní ọjọ́ kínní osù kejì ọdún 2021) jẹ́ akọ̀ròyìn Nàìjíríà àti olóṣèlú kan tí ó jẹ́ Mínísítà fún ìfitónilétí àti àṣà Nàìjíríà (láti ọdún 1986 wọ 1990) lákòókò ìjọba ológun tí Ọ̀gágun Ibrahim Babangida.Ibi àti Èkó a bí Momoh ní ọjọ́ 27 Oṣù kẹrin ọdún 1939 ní Auchi, ìjọba ìpínlẹ̀ Ẹdó..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ karùn-ún lé lọ́gọ́jọ (165) tí ọba Momoh í ti Monkàn..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé ìjọba ránkẹ̀ (1949–1954) àti ilé-ìwé Anglican Okpe (1954)..
wikipedia
yo
Momoh jẹ́ olukọni akẹ́èkó ní ilé-ìwé Anglican, Monfo (oṣu kínní- Oṣù kejìlá 1955) àti Olùkọ́ni ní ilé-ìwé Anglican, Ubuneke, IVbíaro, Ijọba Ibile Owan (January 1958 - Kejìlá 1959).Awon Ìtọ́kasí àwọn ọba àti ijoye ní Nàìjíríàawọn ọmọluwabi ara Nàìire Ojol Ojol ni 2021 ní 1939..
wikipedia
yo
Robert Campbell (tí a bí ní 7 May 1829 - 19 January 1884) jẹ́ ọmọ bíbí Orílẹ̀ Èdè Jamaican tí ó fi ìgbà kan gbé ní orílẹ̀ èdè United States kí ó tó lọ sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
ní àkọ́kọ́ ó kọ́ ṣe lábẹ́ atẹ̀wéjáde kí ó tó kọ ṣe láti di olùkọ́ ti èdè Spéìn nígbà tí ó ri pé ọwọ́ oṣù òun kéré nínú ìdàrúdàpọ̀ ọ̀rọ̀ ajẹ́ Post-Abotion Jamaica, ó kó lọ sí orílẹ̀ èdè Nicaragua and Panama kí ó tó wá tẹ̀dó sí orílẹ̀ èdè New York ní ọdún 1853..
wikipedia
yo
O sise bi atẹ̀wéjade ki won to gba si ise gege bi oluko imo Science leyin naa odi igba keji oga ile iwe Institute for Colored Youth ni Philadelphia Pennsylvania.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Simon Kọ́láwọlé jẹ́ akọ̀ròyìn, Asọ̀rọ̀-lórí-ìtàgé, àti oníyàrádíà aládàáni ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti olùdarí ní Cable Newspaper Limited, lábẹ́ The Cable, iléeṣẹ́ ìwé Ìròyìn Orí Afẹ́fẹ́ aládàáni..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, Àjọ Ètò Ọrọ̀-Ajé Lágbàáyé “The World Economic Forum" pe Simon Kọ́láwọlé ní ọ̀kan lára àwọn ọ̀dọ́darí lágbàáyé, èyí Young Global WaWAA gẹ́gẹ́ bíi ẹ̀yẹ ìdánimọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ àti ìfọkànjìn rẹ̀ sí àwùjọ..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí Daily Trust ṣe ṣe àfihàn rẹ̀, nígbà tí Kọ́láwọlé wà ní ọmọ ọdún mọkandinlọgbọn, ó di ẹni tó kéré jù lọ lọ́jọ́ orí tó jẹ́ àṣàtúnṣe sí ìwé ìròyìn àpapọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007, ẹ̀wẹ̀, nígbà tí ó di yíyan gẹ́gẹ́ bíi Asatúnṣe fún ìwé ìròyìn This Day, Ó tún jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tó kéré jù lọ tí ó ní irú àṣeyọrí yìí.Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbé-ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìlú Ìlọrin ní Ìpínlẹ̀ Kwara, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n gbé bí Kọ́láwọlé Simon, ṣùgbọ́n ó sì lọ sí ìlú mọ́pa ní ìpínlẹ̀ kogi láti gbé pẹ̀lú arúgbóbìnrin rẹ̀ lẹ́yìn tí baba rẹ̀ kú ní inú ìjàmbá ọkọ̀ ojú ọ̀nà ní ọdún 1976..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1989, ó padà sí ìlú Èkó láti lọ kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní inú Mass Communication ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Fásitì ti ìlú Èkó èyí University of Lagos.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
síwá Udobang, tí a tún mọ sí síwáná síwáná, jẹ́ akọ̀ròyìn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó tún jẹ́ akéwì, oníròyìn, òṣèré àti òṣìṣẹ́ amóhùnmáwòrán..
wikipedia
yo
Iṣẹ rẹ ti han ni ori BBC, Al Jazeera, Huffington Post, BellaNaija, ati the Guardian, won se apejuwe re gege bi i “Ọ̀kan lára àwọn tó dáato lẹ́nu kí a sọ̀rọ̀ tó múná dóko.”Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Abidínà Coomassie jẹ́ akọ̀ròyìn àti atẹ̀wé-ìròyìn jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.ìgbésíayé àti iṣẹ́ rẹ̀ Coomassie ni ó da today's Communications Ltd sílẹ̀, tí ó ń ṣalojáde ìwé-ìròyìn bíi Defunct today, ìwé-ìròyìn ojoojúmọ́ tí Abuja Mirror àti èdè Hausa, a Yau.A bí i sí ìdílé Ahmadu Coomas, tó jẹ́ alábòójútó àti akọ̀wé ní apá àríwá Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Arákùnrin ló jẹ́ ọ̀gá Ọlọ́pa tẹ́lẹ̀, Ibrahim Coomas..
wikipedia
yo
GẸ́GẸ́ BÍ oníṣẹ́ ìròyìn, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ní Ghana Broadcasting Service lásìkò ìjọba Kwame Nanimah, lẹ́yìn tí ó kúrò ní Ghana, ó dara pọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ Radio FRCN, Kàdúná lẹ́yìn náà ó sì ṣe ìròyìn nípa ohun Abẹ́lẹ̀ Nàìjíríà níbi tó ti bá ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ ológun tí wọ́n yóò tún gba òṣèlú àwọn ipa .àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
StuMai Abdalla jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Tanzania tí ó ṣeré ipò iwájú lórí pápá fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin Tanzania ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2019, ó jẹ́ aṣáájú fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè nígbà tí wọ́n n jà fún Ifẹ̀ ẹ̀yẹ ìdíje idùnnù Women's Championshipàwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn aláàyè..
wikipedia
yo
Tẹji daba Chalchissasa ni a bini ojo ogun, oṣu August, ọdun 1991 jẹ elere sísá lobinrin to ṣoju fun Bahrain..
wikipedia
yo
Matilda Kerry jẹ́ onímọ̀ ìṣègùn òyìnbó àti asọ̀rọ̀ lórí ẹ̀rọ ìmọ̀hun máwòrán, ó wà lára àwọn tí ó ń ṣe ètò The Doctors..
wikipedia
yo
Ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ obìnrin tó rẹwà jù ní Nàìjíríà ní ọdún 2000.Èkó Kerry lọ ilé ìwé Federal Girls College, ti Benin, ibẹ̀ ni ó ti gba ìwé ẹ̀rí wáEC rẹ̀..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà tí ó parí ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírì rẹ̀, ó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásitì ìlú Èkó láti kọ́ nípa ìmọ̀ ìṣègùn òyìnbó.Iṣẹ́ rẹ̀ Kerry kàwé gboyè ní Yunifásitì ìlú Èkó ní ọdún 2006 láti di Dókítà alábẹ́rẹ́..
wikipedia
yo
Òun ni Ààrẹ George Kerry Life Foundation, àjọ tí ó ń kọ́ àwọn ènìyàn nípa àwọn àìsàn tí kò ṣe kò ran.Ó wà lára àwọn Young African Leaders Initiative, ètò tí Ààrẹ Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀rí, Barack Obama dá kalẹ̀.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
FirehIwọt Tufa Tẹ́ru ni a bini ọjọ Kẹsán, oṣu January, ọdun 1984 si AsSela, Arsi jẹ elere sísá lobinrin ti ona jinjin..
wikipedia
yo
Birhan Dagne ni a bini ojo kejo, osu April, odun 1978 je elere itage lobinrin je omo bibi ile Ethiopia sugbon to gbe ni ile British ..
wikipedia
yo
Arabinrin naa da lori ere sisa ti ona jinjin.aṣeyọridagne kopa ninu idije agbaye Junior ti IAAF ti oju ọna ni metres ti egberun meta ati metres ti egberun mewa.Birhan ṣoju fun Britain to si kopa ninu idije agbaye ti IAAF ni odun 1999.Ni odun 2004, dagne kopa ninu Marathon ti London larin iṣẹju aya ẹyọkan.itọkasi..
wikipedia
yo
Oṣèèṣìtu daska MoLisa ni a bini ojo kerin leelo osu October, odun 1983 e elere sísá lobinrin orile ede Ethiopia to da lo ri ti ayeye ere sísá ti oju ona.Daska gba ami eye ti ọla lẹẹmeji ninu idije agbaye ti IAAF..
wikipedia
yo
Bizirun débá ni a bini ọjọ kejo, oṣu September, ọdun 1987 jẹ elere sísá lobinrin ti ilẹ̀ Ethiopia tó dá lórí eré sísá ti ọ̀nà jínjìn..
wikipedia
yo
Ramadan (Ramzan, Ramadhan tabi Ramathan) jẹ́ oṣù kẹsan-an ninu ònkà oṣù ojú orun ẹ̀sìn ìmàle..
wikipedia
yo
Gbogbo ẹlẹ́ṣin Islam ninwọ́n ma n gba ãwẹ̀ nínú oṣù Ramadan jákè-jádò àgbáyé, tí wọ́n sì ma ń kún fún bíbẹ Ọlọ́run púpọ̀ jùlọ..
wikipedia
yo
Gbígba awẹ́ ninu oṣù Ramadan lọdọọdun jẹ́ ìkan ninu àwọn opó maruun ìmàle..
wikipedia
yo
wọn ma n gba ãwẹ̀ nínú oṣù Ramadan fún ọgbọ̀n ọjọ́ tàbí ọjọ́ mọkandi..
wikipedia
yo
Bíbẹ̀rẹ̀ aṣọ́bodè má ń dá lé bí wọ́n bá ṣe rí ìlétéṣù lójú ọ̀run níparí oṣù sha'àbáàṣà..
wikipedia
yo
Bí wọ́n bá sì fẹ́ túnù, wọn yóò ma wòye ojú ọjọ́ fún lílé oṣù oṣù Shawwa tàbí kí wọ́n ka awẹ́ Ramadan pé ọgbọ́n gbáko kí wọ́n tó dáwọ́ awẹ́ dúró.Gbígbà láti òwúrọ̀ kutukutu ti ti di ìgbà tí òòrùn bá ti wọ̀ tán, jẹ́ dan dan fún gbogbo mùsùlùmí tí wọ́n ti bàlágà yí wọn kò sì ní ìṣòro àárẹ̀, tàbí àìsàn tó lágbára, tí wọn kò sì sí ní inú ìrìn-àjò tó lágbára, tí wọn kò sì kìí ṣe arúgbó kúgì kúgì, bákan náà tí wọ́n kò sì kìí ṣe abiyamọ tí wọ́n ń fọmọ lọ́yàn tàbí ṣe nkan oṣù lọ́wọ́..
wikipedia
yo
oúnjẹ tí wọ́n ma ń jẹ ní ìdájí ni wọ́n ń pè ní sààrì nígbà tí oúnjẹ tí wọ́n ma ń jẹ tí wọ́n fi ń sínú ni wọ́n ń pè ní ìṣínù..Àwọn ìtọ́kalórílé..
wikipedia
yo
Eleanor ńwá jẹ́ dókítà alábẹ́rẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ajà fún ètò ìlera tó péye fún àwọn obìnrin..
wikipedia
yo
Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí a kọ́kọ́ yàn gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Medical Women International Association.Ìpilẹ̀ rẹ̀ baba Eleanor jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Ábíá, Nàìjíríà, ìyá rẹ̀ sì wá láti orílẹ̀-èdè Jamaica..
wikipedia
yo
Awon mejeeji pade ni London nigba ti baba re n ko nipa imo isegun oyinbo ti awon ẹranko ni Yunifasiti ti London ati ti iya re n ko nipa ise Nursi.Eleanor lo opolopo ile-iwe nitori ise ti baba re n se ati nitori ija abele Naijiria..
wikipedia
yo
O lo ile iwe Queen's School, Enugu; Saint Louis Grammar School, Ibadan; ati International School, Yunifasiti ilu Ibadan..
wikipedia
yo
Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìṣègùn òyìnbó ní Yunifásítì ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú láti gba àmì-ẹ̀yẹ Master's degree nínú ìmọ̀ ètò ọmọ ènìyàn ní European Inter-University Centre, Venice, Italy.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mamman Daura (ti a bi ni ọdun 1939) jẹ olootu iroyin ti Naijiria ti o se àtúnkọ, ti o pada se iṣakoso Naijiria tuntun lati ọdun 1969 di 1975..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n sí Ààrẹ Muhammadu Buhari àti ọ̀kan gbòógì ọmọ ẹgbẹ́ Kaduna Mafia, ẹgbẹ́ Aláìmúnisìn oníṣòwò, òṣìṣẹ́ ìlú, ọ̀jọ̀gbọ́n àti Olórí ológun láti ilẹ̀-àríwá Nàìjíríà.Ìgbésí ayé rẹ̀ a bí Mamman Daúo ní Daúura, ilẹ̀ àríwá, British Nigeria ní ọdún 1939, baba rẹ̀ Alhaji Dadá Oura di oyè Durbin dá ti dá _ ó sì jẹ́ ẹ̀gbọ́n Muhammadu Buhari Buhari..
wikipedia
yo
Ó kéẹ̀kọ́ ní Dáura Elementary school, Kat Middle school kí ó tó lọ sí Prospects Secondary school, Okene..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1956, nigba to pe ọmọ ọdun mẹ́tàdínlógún, o bẹrẹ sii ṣiṣe pẹlu Daura Native Authority fun ọdun diẹ ki o to darapọ mọ Nigerian Broadcasting Corporation..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ilẹ̀-Ariwa mẹ́fà ti sir Ahmadu Bello yàn láti kẹ́kọ̀ọ́ ní Englandàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Worknesh E°FA ti a bi ni ọjọ kejidinlọgbọn, oṣu kẹwàá, ọdun 1990 je ọmọbinrin to n kopa ni nu ere sísá ti ona jinjin ni orilẹ-ede etpia..
wikipedia
yo
Olayinka Kokòso-Thomas (tí a bí ní ọdún 1937) jẹ́ Dókítà alábẹ́rẹ́ tí a bí ní Nàìjíríà ṣùgbọ́n tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè Sierra Leone..
wikipedia
yo
Wọ́n mọ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ orílẹ̀-èdè fún ipá rẹ̀ láti dá sì ṣe abẹ́ ojú ara àwọn ọmọbìnrin jòjòló dúró..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1998, ó gba àmì-ẹ̀yẹ Prince of aṣtuyanrìn Award fún iṣẹ́ rẹ̀.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
yíhùnlish delelecha tí a bí ní Ọjọ́ kejìlélógún Oṣù Kẹwàá, Ọdún 1981 jẹ́ ọmọbìnrin tó n kópa nínu eré-idaraya ti eré-Sísá, ní orílẹ̀-èdè Ethiópíà..
wikipedia
yo
Arabinrin naa kopa ninu idije Agbaye ti ere-sísá to si gba ami-ẹyẹ ti Silver fun ilẹ̀ Ethiopia.Ni ọdun 1998, Delelecha kopa ninu idije ti IAAF to waye ni Ilu Marrakemúrash, ni Orilẹ-ede Morocco, nibi to ti ṣoju fun ile Ethiopia..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, Delécha kópa nínu Marathon tí Houston tó sì gbé ipò kẹta..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2012, Delelecha kopa ninu ere to waye ni Washington D.C..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, arábìnrin náà kópa nínu idaji Marathon ti Pittsburgh tó sì gbé ipò KẸRIN..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2012, yíhùnlish kópa nínu idaji Marathon ti Philadelphia tó sì gbé ipò kẹrin..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2013, Delelecha kopa ninu ere ti Pittsburgh to si pari pẹlu ipo kẹta.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Shure lórí ware tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún Oṣù Kìíní, Ọdún 1996 jẹ́ ọmọbìnrin tó ń kópa nínu eré-idaraya eré-Sísá ní orílẹ̀-èdè ethopia, tó sì ti kópa nínú ìdíje lórílórí.àṣení ọdún 2015, ibàjẹ́ kópa nínú Marathon ti Dubai tó sì parí pẹ̀lú ipò kẹrin..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2015, Doko kopa ninu Marathon ti ile Boston to si pari pẹlu ipo kejo..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2019, Dranti kopa ninu Marathon ti awọn obinrin ni idije Agbaye lori ere Sísá to waye ni Doha, Qatar.awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Mérìmà Denkà tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún osù kẹjọ́, ọdún 1974 ní ìlú Arsì jẹ́ ọmọbìnrin eléré sísá tẹ́lẹ̀ rí, tó dá lórí ẹgbẹ̀rún-un mítà.Àwọn ìdíje àgbáyéàṣeyọríni ọdún 2003, DenBóbá yege nínú Oìíra ti àgbáyé tó sì tún yege nínú Cross Internacional dé Itali ní ọdún náà..
wikipedia
yo
Arabinrin naa pada wa fun aṣeyọri keji ni ọdun 2004.Awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, BirHanhan ni a yàn gẹ́gẹ́ bíi ọ̀kan lára àwọn obìnrin tó yege nínú eré ṣísá ní ìdíje àgbáyé láti sojú fún ẹgbẹ́ eré ṣíṣí àwọn obìnrin ti ilẹ̀ Ethiópíà..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2017, BirHanhan kopa ninu idije Agbaye ti ere sísá ninu Marathon ti awọn obinrin.Awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Benin - batism Cerect in Cotonou.jpg Celestial Church of Christ ti a tun mọ si ijo mimo ti Kristi(CCC) jẹ́ ilé-ijọsin tí Samuel Oshoìrètí dá sílẹ̀ ní Afrika ní ojo 29 Oṣù kẹsán-an ní ìlú Porto-Novo, níH Benin..
wikipedia
yo
Ó wà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé pẹ̀lú orílẹ̀ èdè America àti àwọn orílẹ̀-èdè púpọ̀ ní Africa.Ìtàn Oshoìpinnu tí a bí sí Dahomey ní ọdún 1909 fìgbà kan jẹ́ gbẹ́nàgbẹ́nà tí ó ti di Benin báyìí..
wikipedia
yo
Ó ní Ìṣípayá àtọ̀runwá nígbà tí ó sọnù sínú igbó ní ọjọ́ 23 oṣù karùn-ún, ọdún 1947 tí ìṣẹ̀lẹ̀ Eclipse ṣe..
wikipedia
yo
O nímọ̀lára lati gbadura, lati mu awọn alaisan lara da, ati lati ji awọn oku dide..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó ti yan ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi wolii, Olùṣọ́-àgùtàn, ati olùdásílẹ̀..
wikipedia
yo
Ipò tí ó ga jù lọ ni ó wà nígbà náà.CEC gba idanimọ ati ase lati tẹsiwaju ninu iṣẹ wọn lati owo orilẹ-ede Dahomey ní ọdun 1965..
wikipedia
yo
Láti ọdún 1976, ìjọ náà bẹ̀rẹ̀ ìpolongo ìhìnrere ní orílẹ̀-èdè yẹn, tó fìgbà kan jẹ́ French West Africa, tó ti gba òmìnira ní ọdún 1960..
wikipedia
yo
Láti òpin ọdún 1960, ijó náà bẹ̀rẹ̀ sí ní lo ẹ̀rọ-ayélujára fún ìpolongo ìhìnrere, èyí sì mú kí ìbánisọ̀rọ̀ wà láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ka ìjọ náà tó ti wà ní ìdásílẹ̀ káàkiri ilẹ̀ òkè-òkun ti ọmọ Africa wà, bíi United Kingdom, Germany, Austria, France àti United States..
wikipedia
yo
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ìjọ yìí gbajúmọ̀ sí.Lẹ́yìn ikú Oshokiri, Ìjọ náà ń tẹ̀síwájú, àmọ́ kò ṣàìrí àwọn ìdojúkọ kọ̀ọ̀kan, èyí tó wọ̀ pọ̀ jù lọ ni ọ̀rọ̀ Olórí àti adarí Ìjọ náà lẹ́yìn ikú Oshoàsáró..
wikipedia
yo
Leyin baba Oshokiri, Alexander Abiodun Adebayo Bada lo je adari ijo naa titi di igba iku re ni ojo kejo osu kesan-an, odun 2000..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà ni Philip Hunsu Ajọ́sẹ̀ gorí ipò náà fún ìgbà díẹ̀, torí ikú rẹ̀ ní oṣù kẹta, ọdún 2001..
wikipedia
yo
Àwọn òwò ènìyàn kan kéde Gilbert Olùwà Jesse gẹ́gẹ́ bíi olórí tuntun, nígbà tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ Reverend Emmanuel Oshoìrètí, tí ó jẹ́ ọmọ Samuel Oshoìpinnu Bada bíi olórí tuntun..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ikú Jesse, ẹgbẹ́ rẹ̀ polongo pé ajíhìnrere gíga jù lọ Paul ṣùrù maforíkan ní aṣáájú ẹ̀mí tuntun ti ìjọ..
wikipedia
yo
ní ìlòdì sí ìlànà ìtẹ́lọ́rùn ní Nàìjíríà, Porto-Novo tó jẹ́ olú ilé-ìjọsìn gíga jù lọ, yan Benoit àgbàóssi (1931-2010) láti jẹ́ olórí ilé-ijọsin, ẹni tí ó wá yan Benoit adéogun ní àkókò tirẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olùṣọ́-àgùtàn láìpẹ́, kí ó tó kú ní ọdún 2010.Ìwé àkọsílẹ̀ (in French) Pierre Nndm, Luya Sur l'Église du christianisme Celeste, Paris (France), 2016, 283 p..
wikipedia
yo
Kapàdé (in French) Claude Wautmúnú, << l'Église du christianisme Celeste >>, in Secuntes et Prophetes d'Afrique Noire, Sed, Paris, 2007, Chapter XV, p. 227 and f..
wikipedia
yo
(in English) Edith Oshoìrètí, the enigmatic spiritual leader of our time s.B.J..
wikipedia
yo
Bọ́sẹ̀dé Bùkọ́lá Abọ́là jẹ́ Dókítà ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ onímọ̀ nípa àìsàn ojú ara àwọn obìnrin, ọ̀jọ̀gbọ́n àti adarí ẹ̀ka àwọn ọlọ́yún àti àwọn àìsàn ti ojú ara obìnrin ní ilé ìwòsàn ti Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó, Èkó, Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun tun ni oludasile ati Alaga Mrh (Ibadannal and reOlówóctive Health) Research Collective.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Aderonke kalẹ̀ jẹ́ dókítà ọpọlọ fún àwọn ẹgbẹ́ ọmọ ológun Nàìjíríà, òun ní obìnrin àkọ́kọ́ láti di májo General ẹgbẹ́ ọmọ ológun Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O wa lara awon adari Nigerian Army Medical Corps.Iṣẹ rẹ Aderonke kalẹ̀ kẹkọọ nípa imo ìṣègùn òyìnbó ni kọlẹji Yunifasiti ti o pada di Yunifasiti Ilu Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, kalẹ̀ tẹ ẹ̀kọ́ rẹ síwájú nínú ìmọ̀ ọpọlọ ní Yunifásítì ti London..
wikipedia
yo
Àwòkọ́ṣe Ọ̀jọ̀gbọ́n Thomas Adéoyè Ubóde, ẹni tí ó jẹ́ Dókítà Ọpọlọ àkọ́kọ́ ní orílẹ̀ Áfríkà ní kalẹ̀ wò kí ó tó fi pinu pé òun fẹ́ di Dókítà Ọpọlọ..
wikipedia
yo
O sise fun igba die ni Britain ki o to pada si Naijiria ni odun 1971.Ni odun 1972, o dara po egbe ologun Naijiria..
wikipedia
yo
Èyí jẹ́ òun tí kò wọ́pọ̀ láàrin àwọn obinrin ní ìgbà náà, pàápàá jùlọ láàrin àwọn obinrin tí ọwọ́ wọn ti lọ òkè lẹ́nu iṣẹ́ wọn..
wikipedia
yo
O padà di Majo General nínú iṣẹ́ ológun tí ó tó fẹhinti ní ọdún 1997.Ìgbésí ayé rẹ̀ wọn bí Aderonke kalẹ̀ ní Ọjọ́ kẹtàlá Oṣù kejì ọdún 1959..
wikipedia
yo
Bàbá kalẹ̀ jẹ́ onímọ̀ ogun òyìnbó, ìyà rẹ sì jẹ́ olùkọ́, àwọn méjèèjì sa ipá wọn láti rí wípé ikalẹ̀ ní ẹ̀kọ́ tó dájú..
wikipedia
yo
Kale lo ile-iwe primari ni eko ati Zaria ki o to te eko re siwaju ni St..
wikipedia
yo