cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Matthew Ashimolọ́wọ́ ti abi ni ọdun 1952 Oṣu Kẹta.oje Olusho Àgùntàn ati Oludari Kingsway International Christian.Ìgbésí ayé ara ẸniAshimolọwọ́ yipada si Kristiẹniti lati inú Islam ní ọmọ ọdún 20 lẹhin iku baba rẹ ṣaaju ki o forukọsilẹ pẹlu ile-iwe Bibeli..Forbes Ìfojú idiyele iye apapọ Ashimolọwọ́ ni o wa laarin $ 6–10 Ndaa.Àwọn akọọlẹ lododun kiCC jẹrisi pe o gba owo-ori lododun ti ps 100,000 ṣugbọn ọpọlọpọ awọn ohun-ini rẹ wa lati tita ti iwe-akọọlẹ Kristiẹni ati awọn akọọlẹ lati Ile-iṣẹ media rẹ, Matthew Ashimo Media £100,000,awọn aiṣedeede ti owoa ṣe iwadii igbimọ Ife-ọfẹ rẹ.ijabọ naa pari pe iwa àìṣedẽdé to dara ati aiṣedeede wa ni iṣakoso ti Ifẹ.. | wikipedia | yo |
Latin tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún Oṣù Kẹwàá Ọdún 1966 (October 15th, 1966) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré aláwàdà àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá ti ìlú Gbọ̀ngàn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà .Igba Ewe àti aáyan iṣẹ́ tíátà rẹ̀ìlù kan tí ó ń jẹ́ gbọngan ni wọ́n bí ní Bọlaji Amúṣan-an sí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún Oṣù Kẹwàá Ọdún 1966.. | wikipedia | yo |
Gbọ̀ngàn jẹ́ olú-ìlú ìjọba ìbílẹ̀ ayédáa ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun Ọ̀lélé èdè Nàíjíríà.. | wikipedia | yo |
ó fẹ́ìyàwó rẹ̀ Ronke Amúṣan-an lọ́dún 1999 Wọ́n bímọ méjì fún ara wọn.. | wikipedia | yo |
Latin bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún 1988, lọ́dún 1992 ni ó kópa pàtàkì nínú eré kan tí àkọ́lé rẹ̀ n jẹ́ "50 50" | wikipedia | yo |
Agba osere sinima agbelewo ati Akin Ogunru ni o ko sinima naa.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1989 ló dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré sinimá àgbéléwò tí wọ́n ń pè ní Antp.. | wikipedia | yo |
Láti ìgbà náà, Bọlaji Amúṣan-an ti kópa nínu àìmọye sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Latin Foundation.Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀50-50 (1992)ẹbun Igbeyawo (1996)FW[4] (1999)nǹkan ọlọ́mọba (2000) N gbẹ̀mù (2001) Mowaọba-R President Òfin Mose (2006).Ile itura (2007)Baba Insurance (2009),ise onise (2009)bàbá Gominbọ̀wọ̀ Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Mosá jẹ́ ọ̀kan lára àwọn omi lẹ́gbẹ̀ Odi ìbílẹ̀ ní ilẹ̀ Nàìjíríà.Ìwúlò Mosa gẹ́gẹ́ bí ońjẹ Ibilẹ̀ pàtó, jíjẹ́ ni Mosa wà fún.. | wikipedia | yo |
Àmọ́,àwọn ènìyàn má ń lọ́lọ́ fún sàráà ṣiṣẹ́ fún àwọn òkú ọrun, nípa fífún àwọn àtẹ́wọ́ gboré.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún ma ń lo òun àti àkàrà láti fi ṣọdún Egúngún.Bí wọ́n ṣe ń jẹ mọ́sáwọn ma ń jẹ Mosa pẹ̀lú ṣúgà, ẹ̀wà àti onírúurú ohun mímu gbogbo tí ó bá wuni.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Fèrèsé jẹ́ ọ̀kan lára ẹ̀yà ilẹ̀ tí ó ma ń wà ní àárín ògiri méjì ilé.. | wikipedia | yo |
Òsì tún lè jẹ́ gíláàsì tí a fi sí ara ọkọ̀ láti lè jẹ́ kí ọ̀yẹ̀, ọ̀hún, tàbí afẹ́ré ó wọlé.Ìyàtọ̀ fèrèsé ayé òde òní àti ayé àtijọ́láyé àtijọ́, ọ̀pọ̀ àwọn fèrèsé ló ma ń jẹ́ pákó tí a figi ṣe, pàá pàá jùlọ ilé tí àwọn aláìní má ń gbé ni wọ́n ma ń fi páànù àlòkù ṣe fèrèsé tàbí lẹ́kún.. | wikipedia | yo |
Ṣùgbọ́n láyé òde òní, àwọn gíláàsì tí ó ń dán gbinrin ni wọ́n ma ń lò láti fi ṣe fèrèsé.Ìwúlò fèrèséfèrèsé wù ló láti jẹ́ kí afẹ́fẹ́ ó wọlé yálà nígbà òru, ó sì yán ma ń jẹ́ kí á sá fún òtútù lásìkò òjò, òye, àti Adéninti Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
ObiRotimi Odunayọ̀ akéréààbọ̀, San, or Rotimi akéréààbọ̀, ni wọ́n bí ni ọjọ́ kọkànlélógún oṣù keje ọdún 1956 (21st July 1956) jẹ́ óṣèlú, agbẹjọ́rò àti Gómìnà ìpínlẹ̀ Òndó lọ́wọ́lọ́wọ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà , Ó jẹ́ Amòfin-Àgbà san tí ó ti joyè Alága àwọn amòfin Nigerian Bar Association lọ́dún 2008.. | wikipedia | yo |
Kí ó tó di gómìnà ìpínlẹ̀ Òndó, ó jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ amòfin, olùjìnmí & àkèrésọ̀rọ̀, a Law firm he co-founded with chief Akin Olujìnmí, a former Attorney General and minister for Justice in Nigeria.. | wikipedia | yo |
O gbápò isejoba ipinle Ondo lowo gomina-ana ti ipinle naa, Olusegun Bakerkóàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Árábà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olórin tí ó di orin Jùjú mú tí wọ́n sì gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní àsìkò tirẹ̀.. | wikipedia | yo |
Òun àti àwọn bí Akanbí Wright, Victor Ọláìyín jọ jẹ́ olórin Jùjú lásìkò náà.. | wikipedia | yo |
Nínú iṣẹ́ orin rẹ̀, ó ṣalábàápàdé Akanbi Wright tí ó ràn án lọ́wọ́ nípa ìmọ̀ràn àti ìtọ́ni lórí iṣẹ́ tí ó yàn láàyò.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, Àràbà jẹ́ ẹni tí ó kọ́ ògbóǹtagí olórin Jùjú Fatai Rolling Dollar níṣẹ́ orin Jùjú kíkọ.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
B s húndẹ̀yìn ti wọn bi ni Oṣu Kẹta ọdun 1934 jẹ gbajumọ oṣelu ati olukọ ọmọ bibi Ogu lati Ilu Badagry ni ipinlẹ Eko lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Nígbà ayé rẹ̀, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi olùkọ́, olùkọ́-àgbà, Kọmíṣọ́nnà ní Ìpínlẹ̀ Èkó àti agbá òsèlú.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Bode Soyọnu ni a bi ni ọjọkejì oṣu karùún, ọdun 1948 (2-05-1948), jẹ onkọwe, elere onise ati ọmọ orilẹ-ede Naijiria.Iṣẹ rẹ gẹgẹ bi onkọwe jẹ olukọ iwe nipa ọmọnìyàn ati ìṣesí àwùjọ.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ òǹkọ̀wé tí o ma ń lo àwọn ọgbọ́n àtinúdá tí a ṣe lọ́jọ̀ pẹ̀lú àṣà àti ìṣe ilé Yorùbá.. | wikipedia | yo |
sọriyín wà lára owó ìpele ìrán àwọn ònkòwé kejì nílẹ̀ Nàíjírìa, tí wọ́n ma n kefin sí ètò ìṣèlú, bí a ṣe lè dára pọ̀ àti lòó fún ìgbéga isẹ́ ìlú àti ènìyàn gbogbo nínú àpilẹ̀kọ wọn gbogbo.. | wikipedia | yo |
Àgbàlá with ọlọ́gbọ́nTàbí oun lo si tun ni oun lo ni "Odu Themes", ati "bodè Sowande Theatre Academy", tí ó jẹ́ ayé ìkọ́ni fún àwọn òṣèré.Ẹbí rẹ̀ó fẹ́yàwó, ó sì bímọ.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
ṣiyán oyèwẹ́ ti wọn bí ní ọjọ́ kini oṣù kejì, ọdún 1961 ní ìta ìdí-ọmọ ní agbègbè mápọ̀ ọjà àja, ní ìlú Ìbàdàn, ní ìpínlẹ̀ Oyo, ní oríilẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Idilé oyeweso ni wọ́n ṣe wá láti agbolé ọlọ́jọ́ ní ìlú èdè ní Ìpínlẹ̀ òsùnó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ Resiyan Oyewe lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ St.. | wikipedia | yo |
Peter's Anglican Primary School, ti o wa ni agbebgé Mokọ́nà-ede, laarin ọdun 1967 si ọdun 1972 leyin ti o pe ọmọ ọdun mefa gbáko.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ girama ti òkè Iraàìgbàgbọ́ Grammar School láàrín ọdún 1973 si ọdún 1978.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí ni ó tẹ̀ síwájú nígbà tí ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ ti Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ìtàn láàrín ọdún 1978 sí 1982, tí ó sì jáde pẹ̀lú ipele gíga jùlọ ẹlẹ́kejì (Second Class Upper).. | wikipedia | yo |
Ó ṣe Àgùnbánirọ̀ rẹ̀ ní ẹ̀ka ìmọ̀ ìtàn àti ẹ̀kọ́ àgbáyé ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Ìlọrin.. | wikipedia | yo |
O si kẹkọọ gboye M.A ati Ph.D ti o soo di omowe ninu imo Intellectual History ni Ile-ẹkọ yi kan naa.. | wikipedia | yo |
Sbaa Oyewe dara po mo Fasiti ilu Eko gege bi olukoo ni odun 1985 gege bi oluranlowo adaẹ̀fọ́ nílé Eko Yunifasiti ipinle Eko ti o wa ni agbegbe ojo, won si fun ni igbega lenu ise re si ipo olukọni oníbo ikeji ni odun 1987 ati ipo olukọni oníbo kinni ni odun 1989.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sọọ́ di olùkọ́ni àgbà ní ẹ̀ka ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìtàn ní ọdún 1992.. | wikipedia | yo |
ó sì tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ oun ìwádí tí tí ó fi gba oyè ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ ìtàn ní ọdún 2004.Àwọn ipò tí ó dìmú nílé-ẹ̀kọ́ LASUipò adarí ẹ̀ka ẹ̀kọ́lásìkò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ àgbà àti ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ ìtàn ilẹ̀ adúláwọ̀ nílé-ẹ̀kọ́ LASU, ṣíyàn di àwọn ipò pàtàkì kọ̀ọ̀kan mú gẹ́gẹ́ bí alẹ́nulọ́rọ̀ ìmọ̀ Èkó nílé ẹ̀kọ́ náà.. | wikipedia | yo |
Randle (1995-1998) ati ojogbon Deji Femi-Pearse (1999-2003).O tun sise labe igbimo alákòóso ẹlẹ́ẹ̀keje ile-eko naa labe adari won Ogbeni Akin Kekere-ẹkùn ti o je Alaga ti pro-Chancellor fun igbimo naa laarin odun 2004 si odun 2006.Ipa re ni uniOsunni odun 2007, Oyeweso darapo mo ile-eko fasiti ti IpinleOsun Osun ni odun 2007 nibi ti won ti fi se adari ati alákòóso agba yányán fun ile-eko College of humanities and culture lati ibere osu kejo odun 2007 si 2011.. | wikipedia | yo |
Lásìkò yí, àwọn iṣẹ́ ìdàgbàsókè nírúurú ní òyewẹ̀ ń gbésẹ̀ láti lè mú ìdàgbàsókè bá ilé-ẹ̀kọ́ náà.. | wikipedia | yo |
Ó dipò oríṣiríṣi mú nílé ẹ̀kọ́ náà láti orí Olùkọ́, alábòójútó ilé-ẹ̀kọ́, alága, adarí ìgbìmọ̀ ilé-ẹ̀kọ́, alábòójútó àgbà, adarí àgbà fún ohun àmúṣọrọ̀ ọmọnìyàn òun ìdàgbàsókè ( Centre for Human Resource Development).. | wikipedia | yo |
O tun se adari eka imo ikẹkọ titi lae-lae (Life-long learning) ati bẹẹ bẹẹ lọ.Àwọn àwùjọ ti o ti jẹ ọmọ-ẹgbẹṣíyán Oyeweso jẹ ikan pataki ninu awọn opo ti o gbe ajo Centre for Black Culture and International Understanding ti o jẹ ẹka keji fun ajo UNESCO, ti o wa nilu Òṣogbo, nibi ti o ti jẹ ikan ninu awọn igbimọ alákòóso ajo naa.. | wikipedia | yo |
O jẹ ikan ninu ọmọ Igbimọ Àjọ Institute for African Culture and International Understanding.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ ìkan lára ọmọ ìgbìmọ̀ àjò Olusegun Obasanjo Presidential Library (oopl), tí ó wà nilu Abeokuta.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ ìpàpàmọ̀ àti alákòóso ìgbìmọ̀mọ̀ fún Àjọ US based Historical Africa Cultural Centre, tí ó jẹ́ àjò onífẹ́ tí kò gbára lé ìjọba tí wọ́n sí gbé ìgạ̀ga àti ìfihàn ìtàn ilẹ̀ òjẹ̀mọ̀-ijọ́un tí ó fi mọ àṣà, iṣẹ́ ọnà, iṣẹ́ ọnà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.gẹ́gẹ́ bí ọ̀jọ̀gbọ́n tó là-laaka láàrín àwọn oníṣẹ ìtàn, oyè pàwe tí kọ́ àwọn ènìyàn tí àwọn náà ti di igi árábà ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ ìlú oríṣiríṣi níbi tí wọ́n wà lóbi iṣẹ́ mọ̀mọ̀ bí ọ̀jọ̀gbọ́n tó là-laaka, oyè-we, ti ṣe ti ṣe iṣẹ́ ìwádí lórí àwọn iṣẹ́ lọ́wọ́ gẹ́gẹ́ gẹ́gẹ́ ti ìwé tí wọ́n ti ju ìgbà lọ.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni ọ̀jọ̀gbọ́n oyèwẹso ti kó àwọn ìwé àpilẹ̀kọ tí wọ́n jẹ́ ẹ̀rí Máàmiséko fún ìmọ̀.. | wikipedia | yo |
Ọ̀mọ̀wé Shafi Lawal tí a mọ̀ sí S.L Edu ni a bí ní ọdún 1911 tí ó sì kú ní ọdún 2002 jẹ́ oníṣòwò ìlúmọ̀ọ́ká àti ajàfẹ́tọ̀ọ́agbègbè ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí.. | wikipedia | yo |
Òun ni olùdásílẹ̀ ètò-ìṣú Àdọ́sókè ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà èyí tí kìí ṣe ti ìjọba tí ó sì máa ń rí sí àwọn iṣẹ́ ìdídìrí.Àyè rẹ̀a bí ọ̀mọ̀wé ìdu ní ìlú Ẹgún sínú ìdílé ìpàdé tí ní Àdù àti Raliatu tí í ṣe ìyá rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ láti ilée-kẹ̀ù kí ó tó di pé wọ́n mú lọ sí ilé-ìwé Musulumi alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti ìjọba ní ìlú Èkó.. | wikipedia | yo |
Ó parí ní ọdún 1927 ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ olùkọ́ ní ilé-ìwé náà.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Oloye Shafi Lawal Edu (1911-2002), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí S.L.. | wikipedia | yo |
Edu,ni o jẹ oṣu lagbo awon o lo ko wo awonke ni ile Naijiria, ati Látinúatigust ọmọ bibi ilu Epe, ni ipinle Eko.. | wikipedia | yo |
Oun ni o da Conservation Fund ilẹ̀ Nàìjíríà silẹ ti o jẹ ajo ti o jẹ ti aladani.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bi ẹrú ní ìlú Ẹ̀pẹ́ sínú ẹbí ọ̀gbẹ́ni láwàní edu; ẹni tí ó jẹ́ aláya púpọ̀ nígbà tí ìyá rẹ Raliatu jẹ́ ọmọ adarí kan nínú ẹṣin Islam.Ìrìn-rin-dò ẹ̀kọ rẹ̀o bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ láti ilẹ̀ kéwu, ṣáájú kí o tó wọ ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ government Muslim ní ìlú Ẹ̀pẹ́.. | wikipedia | yo |
Ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ọdún 1927, tí ó sì padà ṣe ṣe olùkọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ tí ó ti jáde.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Bike ayo Mọ́gàjí ni wọ́n bí ní ọdún 1964 jẹ́ gbajúgbajà òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ sinimá àgbéléwò, Shaibú túmọ̀Ìlúìlú ṣe sọ, bíb ayọ̀ Mọ́gàjí ti kópa nínú sinimá àgbéléwò, eré-ìtàgé, àti eré àṣà fihàn Orí tẹlifísàn tó ti tó ẹgbẹ̀rin (800).Ìgbà èwe rẹ̀ wọ́n bí Born Bta Ayọ̀ Mọ́gàjílọló 1964.. | wikipedia | yo |
O je omo bibi agbo ni iluIbadan ni IpinleOyo lati orile edeNaijiria.. | wikipedia | yo |
Baba jẹ́ àlùfáà Mùsùlùmí, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́ àgbà.. | wikipedia | yo |
Ayọ̀ fẹ́ gbábọ́ọ̀lù-fẹ̀yìntì àti eléré ìdárayá, Victor Ayodele Odugo.. | wikipedia | yo |
Kí ó tó lọ́kọ, òun àti gbajúmọ̀ òṣèré mìíràn, jíbọ̀ ẹlẹ́kú n ṣeré ìfẹ́ tí wọ́n sìn bímọ kan fún ara wọn.Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀ kakékeré (2019) Pásítọ̀ Deíndé (2005) àkọ́bí gómìnà 2 (2002) ẹni ẹlẹ́ni 2 (2005) Nowhere to be found Why Ogu the Barber? Sergerin Okoro Aibùsùngi Mojèrè Owo Blow ti Oluwa nile (1992) Motherhood Owo ale Ìlẹ̀kẹ̀ ojuju ilẹ̀ olórogún Checkàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Baṣọ̀run Gáà jẹ́ Olóyè Alágbára Ìlú Ọ̀yọ́ Láyé Àtijọ́.. | wikipedia | yo |
Nígbà ayé rẹ̀, gàá burú débi pé Aláàfin Ọ̀yọ́, tí ó jẹ́ ọba aládé bẹ̀rù rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Òun ni òǹkọ̀wé Adébáyọ̀ Fálétí kọ nípa rẹ̀ nínú ìwé eré-oníṣe tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní Baṣọ̀run Gáà lọ́dún 1972.. | wikipedia | yo |
Níbi tí Baṣọ̀run Gáà burú dé òwe Yorùbá kan jẹmọ́, òwe náà lọ báyìí; “Bọ́ o láyà, kò ṣèkà, bó o bá rí Ikú Ọmọlẹ́yìn, kò sòòtọ̀", Yorùbá máa ń fi òwe yìí kìlọ̀ àtúnbọ̀tán ìwà ìkà. Ìta Baṣọ̀run Gáà bí àkọsílẹ̀ kan ni BBC, ìtàn fi yé wa pé, Baṣọ̀run Gáà ni olórí ìgbìmọ̀ Ọ̀yọ́mèsì, èyí tó dàbí olóòtú ìjọba láyé òde òní, lẹ́yìn Aláàfin, tíí ṣe Oriade ìlú Ọ̀yọ́, Baṣọ̀run gorí ló tún kú.Kò sí ṣeni tó le è sọ pé tí Baṣọ̀run kọ́ Do kọ́ èèyàn gidi, wọn yóò fi jẹ́ oyè Baṣọ̀run, tó jẹ́ olórí Ìgbìmọ̀ Ìgbìmọ̀ fún Aláàfin, tíí ṣe Ọ̀yọ́mèsì. Ní báyìí, ó wá yé ka ìtàn àti ìtàn akọni akọni yìí àti ipa tó kó ní ìlú rẹ̀, bóyá rere ni Àbí búburú. Ggíga ni olórí ogun Ọ̀yọ́ ilẹ̀ àti gbajúmọ̀ ìlú ni sáà ònkà ọdún kẹtàdínlógún sí ìkejì sí ìkejì/ Arábìnrin Century, ṣe gudugudu ṣe gudugudu méje àti ya ní mẹ́fà láti ríi ṣe èyí ṣe Ọ̀yọ́ ilẹ̀ di ìlú ńlá, ó lágbára, tó sì fẹ́ dé ọ̀pọ̀ ìlú àti orílẹ̀-èdè lóde ni ◆ ní Aláàfin ni yòó sí láti di ìdáni, olóòtú ìjọba àti olórí ìgbìmọ̀ Èkó Èkó àti ṣe Alágbára náà ni ilẹ̀ ilẹ̀ tí agbára sì ń pa ó bí ọtí ilẹ̀ ilẹ̀ kan, ó k sínú, ó tùṣẹ tí Adémo * ti Ọ̀yọ́ sì máa ń gba ìwọ̀n láti ọ̀pọ̀ ìlú tó wà lábẹ́ rẹ̀- tàgbà rẹ̀ ló*_ | wikipedia | yo |
jẹ́ ìkòkò tí wọ́n fi ń se ọbẹ̀ láyé àtijọ́ láwùjọ Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Ẹnu ìṣasùn máa ń fẹ̀ dáradára ju ìkòkò lásán lọ, ó sìn máa ń ní ìdérí.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ bíbí akọrin apálà tí ó ti di olóògbé, Haruna ìṣọ̀lá.. | wikipedia | yo |
Gbajúmọ̀ rẹ̀ Gbòde kan nígbà tí ó ṣe àtúnkọ orin bàbá rẹ̀ kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ “sóyòyò” lọ́dún 2004.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Olamide Adedeji ti a bi ni ojo keedogun osu keta,odun 1989 (15-3-1989), ni agbegbe Bariga ni Ipinle Eko ti inagijẹ rẹ n jẹ Olamide Bode tabi BadFilísínì, jẹ gbaju gbaja olorin hip-hop, ọmọ orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ olórin hip-hop tí o n akọrin pẹ̀lú amúlù-ma la èdè Yorùbá àti èdè Gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
ní ọdún 2011, ó ṣe àgbéjáde àwo orin kan Rapsódì lẹ́yìn tí ó tọwọ́bọ̀wé coded túnES.. | wikipedia | yo |
YBNL, tó jẹ́ orin ẹlẹ́ẹ̀kejìré jáde lábẹ́ ẹ̀gbẹ́ orin rẹ̀ “Yahoo Boy No Laptop” tí a tún mọ̀ sí YBN Nation.. | wikipedia | yo |
Ni ojo keje osu kokanla, odun 2013, o se agbejade awo orin ẹlẹ́ẹ̀kẹta re Baddest Guy ever liveth.. | wikipedia | yo |
Orin àdàko re "Durosoke" àti "Yemi my Lover" jáde nínú àwo orin náà.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù keje, ọdún 2013, Olamide jẹ́ olórinàkọ́kọ́ tó máa tẹ́wọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Ciroc.Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ gegege bí Arina bí Ọlákojú Gbenga Adedeji si Bariga, ìpínlẹ̀ Èkó, ní ọjọ́ karundinlogun, oṣù kẹta, ọdún1989.. | wikipedia | yo |
Òun ni ọmọ kejì láàárín àwọn ọmọ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ti pa Adedeji àti ìyàwó kejì rẹ, Ronke Oganya Adedeji bi.. | wikipedia | yo |
Olamide ni aburo meji, oruko ikan n je temmyGold ekeji si n je Eniola Olamikan (ti a tun mo si DJ enimoney).Olamide gbe orin ti akole re n je ' eni duro' jade labe ile-ise rinrin jade coded tun labẹ akoso id Cabasa ni odun 2010.. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ Mass Communication ní Tai Solãrín University àmọ́ kò kà á gboyè torí owó ìṣúná.Adedeji fẹ́ ababìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Adébùkúnmi Aisha Sulemanman.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì jọ bímọ méjì, tí orúkọ wọn ń jẹ́ Maximilian bọ̀lúwatí àti tún pin Myles... | wikipedia | yo |
Orin "Ẹni Dúró" Lo gbé Olamide sí ipò gíga laarin awon olorin hip-hop alitieli èdè Nàìjíríà.Àtòjọ àwọn orin rẹawo orin rẹ RapSodi (2011) YBNl (2012) Baddest Guy Ever Liveth (2013) Street Ot (2014) èyàn May (2015) The Glory (2016) Lagos Nawa (2017) Carpe Diệm (2020) Uy Qti (2021) Unruly (TT) Orin àjùmọ̀kò àti Eps the Kings 2 Kings (With Phyno) (2015) YBN (feet Mafia Family) (2018) - giga Penhauy (2010, Phyno, Check I RHHHH) (2020) Badder Dan (feet (feet) (2013) (Àtòjọ Àwọn Àmì-Eye Waila Ìtọ́kasí in olorin Naijiria.. | wikipedia | yo |
Debora Adébọ́lá Fasoyín ni wọ́n bí ní ìlú Ọ̀yọ́ ní ọdún 1944, sí ìdílé pa afọ̀bimona.. | wikipedia | yo |
O jẹ kèfèrílàwọ́n ọmọ obìnrin àti àbíkẹ́yìn ọmọ nínú ẹbí náà.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọrin ijó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ láti inú ijó Micheal Anglican Church gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ akọrin ijó, ó dara pọ̀ mọ́ Ìjọ C.A.C ní ọdún 1961 lẹ́yìn tí ó ṣègbéyàwó pẹ̀lú ọkọ rẹ̀ tí ó jẹ́ ọmọ ìjọ C.A.C, tí ó sì mú iṣẹ́ orin kíkọ lọ́kùnkúndùn.. | wikipedia | yo |
Ṣísì Olúwasoyín (bí ó ti fẹ́ kí wọ́n má pèé) ni ó jẹ́ adarí ẹgbẹ́ akọrin obìnrin rere nínú ìjọ Christ Apostolic Church, ní ìlú Ìbàdàn ní ọdún 1970, àmọ́ ó di gbajú gbajà akọrin ní ọdún 1980 lẹ́yìn tíó ṣe àwo rẹ̀ tó gbé jáde ọdún n lọ sópin.Ẹbí rẹ̀Dèbórà faṣọyín ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọ̀gbẹ́ni gbẹ̀réyín tí ó jẹ́ ọmọ ìjọ C.A.Àwọn ìtọ́kasí ó bí ọmọ mẹ́rin, ó sì ní ọmọmọ pẹ̀lú… | wikipedia | yo |
Orin ọdún ń lọ sópin ni orin ti ẹgbẹ́ akọrin obìnrin rere ti ijó C.A.C gbé jáde lábẹ́ ìdarí Debora Adébọ́lá Fasoyín lọ́dún 1979.. | wikipedia | yo |
Orin ‘Ọdún ń lọ sópin’ yí jé orin tí wọ́n fi èdè Yorùbá gbé jáde, tí ó sì rinlẹ̀ gidigidi.. | wikipedia | yo |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ló ma ń lo orin yí gẹ́gẹ́ bí orin àdúrà láti fi ṣe ìpalẹ̀mọ́ fún Ọdún Tuntun.Àkójọpọ̀ Àwọn akọrin náààwọn akópa nínú orin yí nígbà náà jẹ́ mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (35), tí wọ́n sì ti dín kù sí méjìlá (12) látàrí bí ikú ṣe ń mú wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ọjà pàṣípàrọ̀ jẹ́ ètò ṣíṣe pàṣípàrọ̀ ohun-ìní tàbí iṣẹ́ láàárín ènìyàn méjì láyé àtijọ́ nígbà tí wọn kò ì tíì ṣẹ̀dá owó fún káràkátà ṣíṣe.. | wikipedia | yo |
Bí àpẹẹrẹ, ẹni tí ó bá ní iṣu ṣùgbọ́n tí ó nílò gàárì yóò wá ẹlòmíràn tí ó ní gàárì tí ó sìn nílò iṣu láti ṣe pàṣípàrọ̀ pẹ̀lú rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ọjà pàṣípàrọ̀ jẹ́ ọ̀nà tí wọ́n ń gbà ṣe káràkátà láyé àtijọ́ láìlo owó.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Owó ẹyọ ni àròkọ tí ó dúró gẹ́gẹ́ bí “òwò” tàbí “àjẹ́” láwùjọ Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Nílẹ̀ Yorùbá, wọ́n máa ń bọ àjẹ gẹ́gẹ́ bí òrìṣà àkúnlẹ̀bọ.Oríkì Ajé Ajé Káàárọ̀ ajé Olókun Ajé OKejìgúlù, Ajé onísó ibojì Akàwé dàgbà Àṣàgba dèwe ẹni tí ẹrù àti ọmọ ń fi ojojumọ wà kiri Ìwọ ni àbámọ̀ tí ó borí ayé Ajé, Ìwọ lajíkí Ajé, Ìwọ Lájige Ajé, Ìwọ lajípé Ẹni àmúsọkún Ẹni Ààkóbá Ìwọ lani ra ọpọlọ arán Aṣọ Ọba ti Ìdà yanranyanran Ajé Àgbà Orisha jẹ́ kí ni lọ́wọ́ Mámíràn kí ni ẹ lọrùn ajé fi ilé mi ṣe ibùgbé, fi ọ̀dẹ̀dẹ̀ mi ṣe ìbúra, àjẹ́ ò rẹ lọ́ ọ.Àwọn ìtọ́kasí | wikipedia | yo |
Jẹ́ ìlànà bí a ṣe ń fi nǹkan ṣe í*. Ọ̀rọ̀ ẹnu láti bá ènìyàn sọ̀rọ̀ láyé àtijọ́.. | wikipedia | yo |
Àròkọ jẹ́ ọ̀nà tí àwọn alágbára, ọba tàbí àwọn olóye ń gbà ṣe ìbánisọ̀rọ̀ sí ara wọn láìlo ọ̀rọ̀ ẹnu.. | wikipedia | yo |
Ènìyàn lásán náà lè parọ́kó ránṣẹ́ sí ẹlòmíràn, tàbí kí wọ́n fi pa àlè lé nǹkan.Aroko pípa ní ayé àtijọ́àròkọ pípa jẹ́ ọ̀nà tí Yorùbá máa ń gbà ṣe ìkìlọ̀ tàbí ránṣẹ́ sí ẹlòmíràn láyé àtijọ́.. | wikipedia | yo |
Àròkọ máa njẹ mọ́ iṣẹ́, ẹ̀sìn tàbí ẹgbẹ́ tí àwọn ènìyàn nṣe.. | wikipedia | yo |
Idi ni yi tíó fi jẹ́ wípé pé ẹnikẹ́ni tía bá fi àròkọ rán gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹni tí ó fetí sí òfin àti olótĩtọ́ ènìyàn.Àwọn àròkọ kan wà tí ó máa ń wà lójú kan, àwọn àròkọ wọ̀nyí ni à npè ní àtẹ̀, irú àwọn àròkọ báyĩ wá láti ṣe ìkìlọ̀ ewu.Láàyè Àtijọ́, oríṣiríṣi àwọn ènìyàn ló máa ń parọ́kò ránṣẹ́.. | wikipedia | yo |
pákó kò ní èròjà kẹ́míkà kan kan tí ó lè pani lára rárá.. | wikipedia | yo |
Ó ń mú àdínkù bá owó níná ní ọ̀nà (0-16%) yàtòọ sí ohun èlò ìfọyín buRoṣi. | wikipedia | yo |
Kànga jẹ́ ihò jíjìn kan tí a gbẹ́ sínú ilẹ̀ létè àti rí omi ilẹ̀ bù jáde fún ìwúlò àti ìmúkúrò ọmọnìyàn àti ẹranko.Ìrísí kàngakànga ni ihò ńlá tí a fi búlọ́ọ̀kù àti sìmẹ́ǹtì mọ yíká ìhò tí a gbẹ́ náà.. | wikipedia | yo |