cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Bákan náà, nígbà tí ó padà sí Nàìjíríà, ó tún bá ilé-ìfowóní Guaranty Trust Bank sísé kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà.. | wikipedia | yo |
Noba ko fi bee rọ́wọ́ mu nigba ti o bere ise sinima agbelewo gege bi olootu, sugbon lodun 2014, ni o sese wa di gbajumo nídìí ise sinima agbelewo.Awon amin eye ti o ti gba ati awon ti won daruko dije re fun Revelation of the Year, Best of Nollywood Award, 2010Best Supporting Actor of the Year 'English', City People Movie Award, 2017The Best Actor in a leading Role 'English' Picture Perfect' Best of Nollywood Awards (B), 2017Best Actor of the Year ‘English’ City People Movie Award, 2018Best Actor of the Year 'English', City People Movie Award, 2018 die ninu awon sinima-àgbéléwò ti o ti kopa Husband of Lagos rat Picture Perfect (2016 film) Road to Yesterday's bá Tiwa's Ahji from to Sani DoBus to Lagos Atlas Atlas a fire in The Rain 30 Di Virgin A Virginawọn ami Abu Awọn Kẹrin Oosu Naijiria.. | wikipedia | yo |
jẹ́ gbajúgbajà olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Ísókó ní Ìpínlẹ̀ Delta lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ẹbí rẹ̀ ni gbajúgbajà olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò tí wọ́n ń pè ní Chico Ejiro lọ́dún 2005, Zeb gba Àmin ẹ̀yẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà Order of the Federal Republic pẹ̀lú gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò lérè Paimo fún akitiyan wọn fún Ìdàgbàsókè sinimá àgbéléwò lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà .àwọn Ìtọ́kasíàwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
, OFR (ti won bi ni osu Kọkànlá odun 1939) je gbajumo osere, oludari ati olootu sinima agbelewo omo bibi ilu Ògbómọ̀sọ́, ni ipinle Oyo lórílẹ̀ ede Naijiria.Awon itọkasiawon eniyan alààyè.. | wikipedia | yo |
Lizzy Ailorin tí orúkọ rẹ̀ gangan ń jẹ́ Elizabeth Ibukun Ailorin (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrin Oṣù Kẹrin) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìjọba ìbílẹ̀ Àgbádárìgì ní Ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Lizzy jẹ́ onisowo bákan naa.Aáyán re ninu ise Tiataleyin tí ó di osere sinima àgbéléwò, ó ti se olóòtú sinimá àgbéléwò mẹ́fà fúnra rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àwọn sinimá-àgbéléwò náà ní Tola gbàràdá; Gold; ìyàwó abuké; pàṣẹd Tinubu; pàṣẹ de first Lady; owó naira bet.Bakan náà, ó ti kópa nínu sinimá àgbéléwò kan bíi; Owowunmi (2010); Arewa Ejò (2009); Iṣẹ́ oníṣe (2009).Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀gbá ọrun jẹ́ ohun tí àwọn ènìyàn okùnrin àti obìnrin Nokun lọlátiláti fi ṣe ọ̀ṣọ́ ara.. | wikipedia | yo |
O tun wa fun sise àdáyanrí tabi iyatọ laarin olówó ati Talika laarin àwùjọ.. | wikipedia | yo |
Ọ̀pọ̀ nínú àwọn ẹ̀gbà ọrùn wọ̀nyí ni wọ́n fi ohun èlò oníyebíye ṣe.. | wikipedia | yo |
Nígé nínú àwọn ẹ̀gbà ọrùn yí ni wọ́n ma ń ṣe pẹ̀lú ìlẹ̀kẹ̀ yálà iyùn ségi, tàbí akọ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Awon Egba ọrun miran ni won di goolu, Idẹ, baba ati awon òkúta oníyebíye miiran se.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
(tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù karùn-ún ọdún 1987) jẹ́ gbajúmọ̀ ajẹsé-gídígbò (mixed Lagos Artist) Ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà tí ó ń Jese onígídígbò jẹun lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.Àwọn ìdíje àti àmì ẹ̀yẹ rẹ̀Kákà ti díje lọ́pọ̀ ìgbà nínú ìdíje ìjà-ẹsẹ̀ onígídígbò tí Ultimate Fighting Championship (UFC)..).. | wikipedia | yo |
Kódà, òun ni olùborí nínú Ìdíje Ìjà Ẹ̀ṣẹ̀-Ònílé ti Ìdíje ọ̀kànlélógún.. | wikipedia | yo |
Títí di ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù kejìlá ọdún 2019, Kakà Usman ni ó wà nípò kẹjọ nínú ìmúsípò àwọn ajẹ́ṣẹ́ onígídígbò lágbàáyé.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ajẹ́ṣẹ́-i-ọmọ bíbí ìlú Auchi ní ìpínlẹ̀ Ẹdó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní Kakà Usman.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí rẹ̀ mú un lọ sí Òkè-òkun, lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà nígbà tí ó wà lọ́mọ ọdún mẹ́jọ.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní níjàwá ní ilé ìwé girama ti Bowíé High School ní ìlú Arlington, ní ìpínlẹ̀ Texas lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Nítorí pé òyìnbó akóni-moonjà kò lè pe orúkọ rẹ̀ gan dá geere, ló bá kúkú sọ kárú Usman ní “Marthy", èyí sìn ní orúkọ tí wọ́n ń pè é nígbà náà.. | wikipedia | yo |
Ní àkókò yìí, ọ̀pọ̀ àṣeyọrí ni Usman ṣe kí o tó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ ní Kọ́lẹ́ẹ̀jì.. | wikipedia | yo |
Jon Jones wà lára àwọn tí Usman bá Jiyaká kí o tó lọ si Kọ́lẹ́ẹ̀jì.. | wikipedia | yo |
Ní Kọ́lẹ́ẹ̀jì, Usman díje ijàkàdi ní ìlú Iowa ní William Penn University fún ọdún kan gbá, ìgbà náà ló tó pegede láti sojú orílẹ̀ ède Amẹ́ríkà nínú ìdíje Naia fún ti ọdún 2007.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, ó kúrò ní Kọ́lẹ́ẹ̀jì náà lọ sí University of Nebraska ní Karney (UNK), Ó sin ràn wọ́n lọ́wọ́ láti gba Àmín-ẹ̀yẹ àkọ́kọ́ lọ́dúndù 2008.. | wikipedia | yo |
Fún odidi ọdún mẹ́ta gbá́, Usman ni ó gba ojú-ẹ̀yẹ ti NCAA Division II All-American Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bí ÀṢAMỌ̀ yí ti wí, àwọn Yorùbá kúndùn láti ṣètọ́jú orúkọ kí wọ́n sì dáàbòbò orúkọ náà kí ó má bàjẹ́.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọmọ ati ọmọmọ pẹlu ẹbí òun ojúlùmọ̀ ló ma ń ṣàjọyọ̀ lórí iṣẹ́ṣe ayé gidi ti òkú lọ ṣáájú kí ó tó tẹ́rí gbaṣọ.. | wikipedia | yo |
Àjọyọ̀ yí kìí ṣe láti ṣe burú tàbí yẹ̀yẹ́ ẹni wọ́n tó lọ, bí kò ṣe láti ṣàfihàn ohun rere àti orúkọ rere tí òkú fi sílẹ̀ẹ lọ.. | wikipedia | yo |
Páá pàá jùlọ, láti fi àsìkò ìkẹ́dùn òun ayẹyẹ sọ gbogbo mọ̀lẹ́bí òkú papọ̀ kí wọ́n lè wà ní ìṣọ̀kan nínú iṣẹ́ wọn gbogbo.Ṣíṣayẹyẹ òkúayẹyẹ ìsìnkú ti bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ tí òkú bá ti kú.. | wikipedia | yo |
Àwọn mọ̀lẹ́bí yóò má dín àkàrà, dín mọ́sá fún àwọn tí wọ́n bá wá bá wọn kẹ́dùn ẹni wọn tó lọ láti àárọ̀ ti ti di ìrọ̀lẹ́.. | wikipedia | yo |
Èyí ma ń wáyé lọ́pọ̀ ìgbà fún ọjọ́ mẹ́ta tàbí méje.. | wikipedia | yo |
Mímú ọjọ́ ìṣàjọyọ̀ ìsìnkú ma ń dá lé bí ebi kọ̀ọ̀kan bá ṣe fẹnu kò sí.. | wikipedia | yo |
Púpọ̀ nínú ẹbí ni wọ́n sábà ma ń yan iṣan tàbí ìtàdógún láàyò lọ́pọ̀ ìgbà fún ayẹyẹ àṣekágbá ìsìnkú láyé àtijọ́.. | wikipedia | yo |
Ṣùgbọ́n láyé òde òní, àwọn ẹbí òkú sábà ma ń fi ọjọ́ gbòòrò tàbí ọdún sílẹ̀ẹ ṣáájú kí wọ́n tó ṣe àṣekágbá òkú wọn.. | wikipedia | yo |
Ìdí èyí ni láti lérò, àti láti wá ohun tí wọ́n yóò fi bọ́ àwọn èrò tó bá wá síbi ayẹyẹ náà.Ẹ̀wẹ̀, ṣíṣayẹyẹ yí kò ní ṣe kò ní ṣe pẹ̀lú ẹ̀sìn, ó kàn jẹ́ wípé ẹ̀sìn kọ̀ọ̀kan ni ó ní ìgbésẹ̀ àti ìlànà tí wọ́n ń tọ̀ lórí irú ayẹyẹ bẹ́ẹ̀ ni.. | wikipedia | yo |
Àmọ́ nínú gbogbo ẹ̀sìn tó gbajúmọ̀ nílẹ̀ Nàìjíríà tí a mọ̀, gbogbo wọn ni wọ́n ń ṣe òkú.. | wikipedia | yo |
Oríṣiríṣi ọ̀nà sì ni àwọn ẹ̀yà tókù náà ma ń gbà ṣe ìsìnkú wọn.. | wikipedia | yo |
(tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 1971)) jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti ìyàwó Ààrẹ Muhammadu Buhari , Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó wà lórí àléfà lọ́wọ́lọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ Buhari gbapò lọ́wọ́ Ààrẹ-àná, Goodluck Jonathan lọ́dún 2015, bẹ́ẹ̀ náà ó tún borí igbákejì Ààrẹ àná nígbà ìṣèjọba Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ , Atiku Abubakar nínú ìdìbò tó wáyé lọ́dún 2019 fún sáà ẹlẹ́kejì.. | wikipedia | yo |
Aisha jẹ́ aṣerunlóge, aṣaralóge àti ònkọ̀wé.Igba èwe àti ẹbí rẹ̀wọn Aisha bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 19711 ní ìpínlẹ̀ adáwà, lápá àríwá orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Bàbá re àgbà Alhaji Muhammadu rìbádu ni Mínísítà Aabo àkọ́kọ́ fún orilẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Akọ́ṣẹ́mọsẹ́ ẹ̀rọ ni bàbá Aisha Buhari, màmá rẹ̀ sin jẹ́ ẹbí Ankali, gbajúgbajà àgbẹ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ.. | wikipedia | yo |
Aisha Buhari kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti girama ní ìpínlẹ̀ adáwàwà.. | wikipedia | yo |
Lọ́jọ́ kejì, oṣù Kejìlá ọdún 1989, Aisha fẹ́ Ààrẹ Muhammadu Buhari lóko, ẹni tí ó ti bímọ márùn-ún pẹ̀lú àkọ́fẹ́ ìyàwó rẹ̀, Safinatu Yusuf.. | wikipedia | yo |
Aisha àti Ààrẹ Muhammadu Buhari bímọ márùn-ún àti ọmọ ọmọ kan ṣoṣo fún ara wọn.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Àkàrà jẹ́ ońjẹ àbínibí ìbílẹ̀ ilẹ̀ Yorùbá àti púpọ̀ nínú ilẹ̀ adúláwọ̀.Ṣíṣe àkàrààkàrà wà nínú ara tí wọ́n ma ń fi ẹ̀wà dá.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ma ń rẹ ẹ̀wà sínú omi, fún bíi ọgbọ̀n ìṣẹ́jú tàbí wákàtí kan kí o lè rọ̀.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, wọn yóo fi ata, àlùbọ́sà, èdè ati àwọn nkan mìíràn tí ó bá wù wá sí kí wọ́n tó lọ̀wọ́n kùnà.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí wọ́n bá loo tán, wọn yóó gbé epo tàbí òróró kaná tí wọn yóò sì ma da ẹ̀wà náà sínú epo yí kí ó lè dín.Bí wọ́n ṣe ń jẹ àkàràwọn jẹ́ àkàrà lásán, wọ́n lè fi jẹ̀kọ, jẹ búrẹ́dì, mùkọ, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ìtọ́kasí nílẹ.. | wikipedia | yo |
(Ti won bi ni ojo kẹẹ̀ẹ́dógún osu keje odun 1967 je omo bibi ipinle Ogun kede ede Naijiria ati iyawo Igbakeji Aare orile ede Naijiria, ojogbon Yemi Osinbajo.. | wikipedia | yo |
Dòwò jẹ́ ọmọọmọ gbajúgbajà òṣèlú àti olórí-òró Ana àwọn ẹ̀yà àwọn Yorùbá, olóògbé Obafemi Awolowo.Igba ewe àti aáyan ìlùlù rẹ̀bẹ́ẹ̀ àti bí ọkọ rẹ̀, DDún jẹ́ amón.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé gboyè gẹ́gẹ́ bí amòfin tí wọ́n fún ún ìwé ẹ̀rí amòfin lọ́dún 1990.. | wikipedia | yo |
Ọdún 1989 ni ó fẹ́ igbákejì Ààrẹ, Yemi Osinbajo lóko.. | wikipedia | yo |
Yato si ise amofin, Dolapo Osinbajo je onkowe, oun ni onkowe iwe kan lede Gẹẹsi ti akole re n je "They Call Me Mama!"Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
jẹ́ ẹgbẹ́ tí àwọn òṣèlú ti ìmọ̀, òye àti èròǹgbà jọra dá sílẹ̀ láti díje dupò òṣèlú ní orílẹ̀ èdè tí wọ́n bá lẹ́tọ̀ọ́ rẹ̀ lábẹ́ òfin.. | wikipedia | yo |
Argi Gbogbo ẹgbẹ́ Òṣèlú ní láti jẹ́ àwọn ipò òṣèlú tí ó bá ṣí sílẹ̀ lórílẹ̀ èdè wọn. Ẹgbẹ́ Òṣèlú tí ó wà ní Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ tí Independent National Electoral Commission|INEC, (FM ẹgbẹ́ Òṣèlú tó wà ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ ọ̀kànlél un (91). Ẹgbẹ́ òṣèlú tó wà lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti 1999 di 2018 Fi wàwà arẹwà Movement (àwa) Action Congress (A AA) Alhaji Party (an (an) Congress of “ Olùke (FMd) For Democracy (AD) for New (FM Ibidele) Democratic Party (Nigeria) ( ADP) Democratic Peoples (AD (AD) Progressives Congress (APC) Democratic Congress (AD AD) Peoples Democratic Alliance (Da All) Progressives Alliance (FM (ga) People Party ( Indu) Party Party [ar] Nigeria Our Oroko [ In Party] People Congress (CP [C Party (FM Nigeria (FM 2008) popular Party (C) S People Party (N-FM Con (FM Mo gbowolori (D) Mo Patv (FM Party (g) Ramón (FM I (FM Party (FM Party) Party (1) Eailar (FM Nigeria (N 2016 (N Party (N) National Interest (FM Ni àwọ̀n (FM FM I (FM Nigeria (PA) Nigeria (Nigeria) for Democracy (FM FM (FM Party (ii) Democratic Party (PDP (PDP) Peoples ( Olùpe (PA Party (P Redels (FM 2010 ( Uaila (4] In E (p to Party to Nigeria (FM R) Democratic * (FM Party (s Nigeria (s film Party (FM S. Nigeria People's Party* | wikipedia | yo |
ohun mímu à£ńlá ohun mímu tí wọn pèsè láti ara àwọn èròjà oríṣiríṣi.. | wikipedia | yo |
Àwọn ohun mimu Fuńlápànìyàn yi le jẹ Coffee, ẹlẹ́rìndòdò bi Co-cola, Mountain Dew, Pepsi ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àtòjọ wọ́nÀwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
WáwáIdi Àyìnlá Yusuf gbogbolọ́wọ́ Better Known as Àyìnlá Ọmọgbọ̀n (1933 – 6 May 1980) was a Nigerian Súnku musician in ìtọ́kọ̀ in 1933 in 1933. Domi Organization Yusuf lọ́wọ́ tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Àyìnlá Ọmọdu (1933– 6 May 1980) Ó jẹ́ ọlọ́rin Àpà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Tí wọ́n bí ní ìtọ́kọ̀, Abeokuta ní ọdún 1933.Àwọn akoonu ọmọgbọ́n jẹ́ ọmọ bíbí inú Yusuf gbogbolọ́wọ́, alágbẹ̀dẹ àti wúràmotu MoreNike.. | wikipedia | yo |
Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní bá baba rẹ̀ ṣiṣẹ́ àgbẹ̀dẹ ṣùgbọ́n tí ó padà kúrò tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ṣe oríṣiríṣi iṣẹ́ bí awakọ̀, alápatà, káfíńtà, ọmọ lẹ́yìn ọkọ̀.. | wikipedia | yo |
Adéwọlé Àlàó onílùọlá wá ṣàwárí rẹ̀, tí ó padà jẹ́ olórí onílù rẹ̀ àti ṣíṣe ẹlẹgbẹ́ ní Ọláṣìkà, nínú ṣíṣe eré àpàlà.. | wikipedia | yo |
MoWúrà was known for !ding with other Muṣicians including his superiors such as Haruna Ishola, whom he later acknowledged to be his superior.. | wikipedia | yo |
He also |deded with Àyìndé Barrister, Fatai Olowonyó, Yesufu Ọlátúnjí and Dáúdà epo àkàrà.These |ds colored his music throughout his Discography.. | wikipedia | yo |
He was noted to have a quick temper and to engage in marijuana use and physical Alterètò.Iku reayinla kú ní ọjọ́ kẹfà oṣù Karùún, ọdún 1980 ní déédé ọmọ ọdún mọkanlelọgbọn (31), látàrí aáwọ̀ ránpẹ́ tó wáyé láàrin òun àti ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀, tí tọ̀hún sì ṣe bẹ́ẹ̀ fọ́ ife ìmumi aláwọ̀ mọ́ lórí tí ó sì gba be ja ṣe tún Ailte.Àwọn ìtọ́kasíàwọn olórin ara Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
ọ̀làjúmole odetola (ti won bi ni ojo kẹrinlelogun osu kewaa) je gbajumo òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orile èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lédè Gẹ̀ẹ́sì, sùgbọ́n ní kété tó dara pọ̀ mọ́ ti èdè Yorùbá ní ìràwọ̀ rè tán.Igbà èwe àti aáyan Ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ Jùmọ̀kẹ́ kàwé girama rẹ̀ ní Abeokuta Grammar School.. | wikipedia | yo |
Ó kàwé gboyè dìgírì rẹ̀ ní ìdásílẹ̀ ti Ajayi Crowther University, níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ìtẹ́tí àti ìṣ̀n nípa lílò ẹ̀rọ ìgbàlódé, Kọ̀m̀ta, lẹ́yìn èyí, ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Federal University of Agriculture, Abeokuta, Abeokuta tí ó ti kàwé gboyè dì ní kejì nínú ìmọ̀ jájá.Àtòjọ Níbe nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀ Some in the Dark Glit Binta Oguta Ops àti Zero Maigi' Egi's Eve Ala Egiga Tinsel The Return of Hoko Family Family City Tape (2017) W Women W (2018) Ìtọ́kasí (2018.. | wikipedia | yo |
Ẹgbẹ́ awakọ̀ ojú pópó (rtwW) jẹ́ Àgbáríjọ ẹgbẹ́ gbogbo ọlọ́kọ̀-ẹ̀rọ tó dá dúró lábẹ́ ẹgbẹ́ oníṣẹ́ ọwọ́ nílẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ègbé yí wà fún láti mú ìṣọ̀kan àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrín àwọn ọlọ́kọ̀-ẹ̀rọ ojú pópó, gẹ́gẹ́ bí àlàkalẹ̀ inú òfin wọn.Ìṣàkóso ẹgbẹ́ wọnÈgbé yí ni àwọn adarí tí wọ́n jẹ́ ti àpapọ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n ní ẹsẹ̀ kúkú (ìpínlẹ̀ sí ìpínlẹ̀).. | wikipedia | yo |
Ààrẹ àti adarí wọn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní Alhaji Tajudeen Baruwa,nígbà tí wọ́n ní àwọn adarí ní ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan.. | wikipedia | yo |
Eni tí ó jé adarí ti Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ́ Musiliu Ayinde Akínsànyà tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Mc Olúomo.Idaran ẹgbẹ́ yí ni akọ̀wé àgbà àpapọ̀ ẹgbẹ́ yí ma ń ṣàtìlẹyìn tí ó sì ń gbẹnusọ láàrin àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àti ìgbìmọ̀ ẹgbẹ́ kí ètò ìṣèjọba tó lọ́ọ̀rìn ó lè wà láàrin wọn.Ọ̀nà ìpawọ̀ ṣẹlẹ̀ wọnÈgbé yí ma ń pawó wọlé sínú àpò ẹgbẹ́ wọn látara ọrẹ àtinúwá ọmọ ẹgbẹ́, nípa gb yìíii gbígba owó ìgbà ní-wọlé ọmọ ẹgbẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Gbogbo ìwọ̀nyí ni eni ti o je oniroyin omo ile American-British Louis theux ṣafihan re ninu 2010 documentary film.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
National Agency for Food and Drug Administration and Control (NAFDAC)jẹ́ àjò tí ó ń rí sí ìakoso ipò oògùn, onjẹ ìbílẹ̀ àti tòkè okun, ohun elo ÌṢARALÓGE (cost), ohun elo ile-iwosan, omi àti bẹ́è bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Àjọ NAFDAC yí wà lábẹ́ àṣẹ àti àkóso Federal Ministry of Health ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ijoba ibile ọjao je okan lara awon ijoba ibile ti lorukọ julo ni Ipinle Eko, ti o wa ninu ilu ojo ni Ipinle Eko, ibè si ni Fasiti ipinle Eko wa.Ìlú ojo wa ni apa iwo oorun ipinle Eko, ni opopona marose ti o lo si ilu AgbaAgba.. | wikipedia | yo |
Ìlú OMELjọ jẹ́ ibùgbé fún tonílé tàlejò, ti oja oríṣiríṣi bí oja gbogbo-gbo Alaba, Alaba Ogo, Oja Ìpàtẹ OKÒWÒ Ìpínlẹ̀ Èkó tẹ́lẹ̀, Oja Iyana-Iba ati Bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ lọ sí gúnwà Sibeitan ìṣẹ̀dá rẹ̀ Àtẹnudẹ́nu fi hàn wípé wípé esú̀, ìyàwó rẹ̀ láàrín ó RIwo Oṣù tí wọ́n wà láti ilé-Ife lati dá ìlú tí wọ́n kọ́ ma pè ní ìlú ni wọ́n tẹ̀ ìlú ojo.. | wikipedia | yo |
èṣùgbemi tí ó jẹ́ òde ní gbèrò láti ta ìlúfẹ́ t í ó di ọjọ́ lónìí ni ó rí agbègbè irà ni ó sọ fún Olúwọ̀ rẹ̀ oṣù tí èyàn náà sì gbéfá janlẹ̀ ní ikémọ́ tí ó di àfìn tí ọlọ́jọ́o lónìí.. | wikipedia | yo |
Ìtẹ̀síwájú àti Ìdàgbàsókè Ìlú yí ni ó mú kí P7pọ̀ nínú àwọn ènìyàn Awori, àwọn ènìyàn Ido àti Idumota tí ó tẹ ilú irewẹ́ ọ̀ṣọ́lu Do Wa tí wọ́n sì n bá wọn gbé pọ̀.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
jẹ́ gbajúgbajà òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún Oṣù Kejì (15th February) ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Bí Fólúkẹ́ ti ń fakọyọ nínú sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá, bẹ́ẹ̀ náà ló dáńgájíá nínú ti èdè Gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa tí ó sìn pegedé.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ìràwọ̀ Ronke kò bá tàn ẹ̀yà LỌ́DÚN 2000 tí ó gbé sinimá àgbéléwò kan jáde tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Ooso-ÒKÈ.. | wikipedia | yo |
In 2015, she released a single Mordekai orí mi which featured 9ice.Àtòjọ die nínu àwọn sinimá-àgbéléwò ResucuBus (2014)Asán Láyéeéṣúàgbèrè Ojúreturn of jẹniadarabùkún AlekoAbeke ẹlẹ́kọ 2:lọ́dàá ẹ̀dà (2006)òkun Ife 2 (2004)òkun Ifẹ̀ (2004)Àṣírí (2002)ọ̀ṣọ́)di Òkè’’ (2000)àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Mercy Johnson Okojie tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹjọ ọdún 1984 (28th August 1984)jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Sinimá àgbéléwò èdè Gẹ̀ẹ́sì àti igbòô ni mercy Johnson máa ń kópa tí ò sìn gbajúmọ̀ nínú wọn.Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀Mercy Johnson-ọkọgíẹ́ jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Okene ní ìpínlẹ̀ kogi, ṣùgbọ́n èkó ni wọ́n bíi sí, jagunjagun orí omi ni baba rẹ̀, ọ̀gbẹ́ni Daniel Johnson, orúkọ ìyá ni Elizabeth Johnson.. | wikipedia | yo |
Mercy bẹrẹ oṣiṣẹ rẹ ni Ilu Calabar ni Ipinle Cross River.. | wikipedia | yo |
O tun kawe ni ipinlẹ Eko Baka naa nigba ti iṣe gbe awọn obi rẹ wa si Eko.. | wikipedia | yo |
Bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé ní Port Harcourt, ní Ìpínlẹ̀ Rivers.Àtòjọ DÍẸ̀ NÍNÚ àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀Àtòjọ àwọn Àmin Ẹ̀yẹ tí ó gbà àti àwọn tí ó díje fúnàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Anayò Modestus Onyekwèrè (tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Kanayo O.. | wikipedia | yo |
Kanayo, ni wọ́n bí ní ọjọ́ kìíní osù kẹ́ta ọdún 1962 (March 1, 1962) ní ìlú Mbaise, ní ìpínlẹ̀ ìmọ̀,lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Gbajumọ rẹ lagbo osere Tiata pọ to bẹẹ gege ti o fi gba amin eye Academy Award 2 Sinimá àgbéléwò olú-ẹ̀dá tí o dára jù lọ Lọ́dún 2006.Akitiyan rẹ gẹ́gẹ́ bí Òṣèréọdún1992, Kanayo iṣẹ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò nínu eré kan tí akole rẹ̀ n je Living in Bondage.. | wikipedia | yo |
Ní báyìí, ó jẹ́ àpàjáde àjò àgbáyé, United Nations ó sìn tún gba àmìn ẹyẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, MFRàwọn ìtọ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
Segun Akanni Ogunru tí wọ́n bí ní ọgbọ̀n ọjọ́, kẹta jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Akin Ògúngbẹ̀ tí wọ́n bí ní ọdún 1934 tí ó sì kú ní Oṣù kọkànlá ọdún 2012 jẹ́ òṣèré orí ìtàgé, adarí eré orí ìtàgé àti agbéréjáde.. | wikipedia | yo |
Ọmọ rẹ ni gbajugbaja osere, olootu ati oludari sinima-agbelewo Segun Ogunruigba ewe ati Aáyán Ìkẹ́kọ̀ọ́a bi ni odun 1934 ni Ilu Abeokuta ti o je olu ilu ipinle Ogun ni apa guusu iwọ-oorun orile-ede Naijiria ti o si ku ni osu kejila odun 2012.. | wikipedia | yo |
Ò n gbé ní ọ̀dọ̀ ìyá ìyá rẹ níbi tí o ti ń kọ́ iṣẹ́ télọ̀.. | wikipedia | yo |
"A Terrible Life" Ni eré orí ìtàgé àkọ́kọ́ rẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ nínu eré náà ni "Bàbá Ibeji ó ti jẹ́ akópa, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò rẹpẹtẹ bi i Ìrèké Onibùdó àti 50-50, ní ọdún 1990 tí òṣèré apanilẹ́rìn-ín Bọlaji Amúṣan-an kópa nínú rẹ̀.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ní bí ọdún 16 Century ní Mọ́ṣáláṣí Neliyeye di kí láti ọwọ́ ayàwòrán ilé kikò, Mimar Sinah.. | wikipedia | yo |
Àwọn ohun ọnà àti ti ẹ̀ṣọ́ ti orílẹ̀èdè náà àti ti Mùsùlùmí jẹ́ ohun àfihàn fún gbogbo ènìyàn eléyí tí ó ti bẹ̀rẹ̀ láti ìṣèjọba Ottoman.. | wikipedia | yo |
Moṣiṣi UC FeliFeli eleyi ti kiko re waye lati odun 15th century, fi egbe tii ile iko ohun ona si yi.itọkasi ] | wikipedia | yo |