cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ile-eko yi kii Ṣàtìlẹ́yìn, tabi ṣe igbelaruge fun ẹgbẹ oṣelu tabi oloselu kan kan bi o ti wulẹ̀ ki o mọ.Engba ile-ẹkọ naaero okan oludasile Ile-ẹkọ yi ni lati mu idagbasoke, iṣẹ àmúyẹ imọ ijinle ti o soodo sinu esin Islam, Títan imọlẹ esin Musulumi kaakiri orile-ede agbaye, kiko ati kikopa awon akekoo esin ati ede larubawa ninu idije, ìpéjọpọ̀Concescesces), ati Iṣẹdi imọ ni awujo agbaye pata.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, wọ́n tún lérò láti kọ́ àwọn ènìyàn àwùjọ ní ìmọ̀ nípa ẹ̀sìn Mùsùlùmí, kí wọ́n sì sí wọn lójú nípa ohun tí ó ta kókó tàbí rújú nínú ẹ̀sìn náà fún àwọn ènìyàn ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí Kari, pàá pàá jùlọ láti lè kọ́ń nípa ètò ìṣèlú, ọ̀rọ̀-ajé, ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn, ìgbé ayé lóko-láyà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ ní ìlànà ẹ̀sìn Islam, nípa ṣíṣe ìṣítí ìta gbangba àtìgbà dégbà.Ẹ̀tọ́ ẹ̀kọ́ wọ́nílé-ẹ̀kọ́ yí ń ṣàmúlò ìlànà ẹ̀kọ́ tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì nínú ìkọ́ni àti ìkẹ́kọ̀ọ́.. | wikipedia | yo |
Oriṣiriṣi iyara Ìkẹ́kọ̀ọ́ ni wọ́n ní tí wọ́n fi ń lọ́mọ pẹ̀lú àwọn olùkọ́.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Femi babaFemi branch ni won bi ni ojo kerinla osu karun un, odun 1970 (14-5-1970).. | wikipedia | yo |
je osere ori-itage, Yoruba ati Geesi,olùkọ̀tàn ati akọ ewi apileko , adari ere ati olùgbéré-jade omo orile-ede Naijiria .Ibẹrẹ Aye ati Eko Kiku bi Femi ni Ilu Sagamu ni Ipinle Ipinle Ogun, sinu ebi Osunkoya ni ọdun 1970.. | wikipedia | yo |
ṣùgbọ́n wọ́n ṣe wá láti ìlú Odòsenbora ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ ìlà oòrùn Ijẹ̀bú.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Satellite Town ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Amuwo Odofin,ní ìpìlẹ̀ ẹ̀kọ́, ṣáájú kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama AirForce ní Ikeja.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí ni ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Ifáfitì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ níbití ó tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ eré oníṣe.Àwọn ìtaọkàsí.. | wikipedia | yo |
Wòlíì àrólé ẹni tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Olúwatoyin bayégún ni wọ́n bí ní ìlú Ìkà-Àkókó ní ìpínlẹ̀ Òndó.. | wikipedia | yo |
jẹ́ òṣèré orí ìtàgé àti Adépopọ̀ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀Olúwatoyin lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ yí ọ̀lapàdé àgòrò tí ó wà ní Àpáta ní ìlú Ìbàdàn, tí ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama Government College.. | wikipedia | yo |
Bakan naa ni o lo si ile-eko ifáfitì Obafemi Awolowo nibi ti o ti gba iwe eri ninu imo sycology.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Aláǹgbá jẹ́ ọ̀kan lára ẹbí langba ti ẹ̀yà wọn tó 300 níyè.. | wikipedia | yo |
Irúfẹ́ aláǹgbá yí wọ́pọ̀ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀, Éṣíà, Australia, àti díẹ̀ ní agbègbè Southern Europe.. | wikipedia | yo |
Ọ̀pọ̀ nínú àwọn aláǹgbá yí ni wọ́n ma ń pè (Mariojìyà) nítorí ìrísí wọn.. | wikipedia | yo |
O fara jo oga, ṣugbọn ti kii yi awo pada bi oga iwadii sayensi fihan pe o to oriṣi ẹgbẹrun mefa oga lo wa kaakiri gbogbo agbaye.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Irun wítiri ninu esin Islam je ẹka kan ninu awon ele irun (naFila), o je irun kan ti a ma n ki ni alaale, leyin irun ishai.. | wikipedia | yo |
Ati pé ó jẹ́ irun ẹyọọ̀kan tì àfi ń parí irun ojúmọ́, lẹ́yìn Shafuhi.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Suhhan tí ó pọn dandan, tí àwọn Onímọ̀ nínú ẹ̀sìn Islam fọwọ́ sí.. | wikipedia | yo |
Irun wítiri ni ó gbọdọ̀ kẹ́yìn gbogbo irun ojúmọ́ ní alaalẹ́.. | wikipedia | yo |
Alausa jẹ adugbo ti o gboro julọ ni aarin Ilu Ikeja ni Ipinle Eko.Ibẹ̀ ni olu ile-iṣẹ ijọba ati ofìsi Gomina Ipinle Eko wa, ti o si jẹ ibùjókòó ọpọlọpọ ile-iṣẹ ni ilu Eko.lara awon ile-ise to laami laaka ti o fidi kale si Alausa ni ile-iṣẹ Cadbury Nigeria Plc, ibè naa tun ni gbàgàn Igba MKO Abiola wa.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Ipaja jẹ́ ìlú kan tí ó kalẹ̀ sí ìlú Èkó ní abẹ́ àṣẹ ìjọba ìbílẹ̀ Alisoso.Ilu náà tóbi púpọ̀ tí osi fi àyè gba àlọ́we ènìyàn tí wọ́n jẹ́ olùgbé yálà ọmọ ìlú tàbí ààrẹ.. | wikipedia | yo |
Orísirísi ilé ìgbafẹ́ àti ìtura ló wà ní ìlú náà pẹ̀lú.Àwọn itọ́ksì.. | wikipedia | yo |
Olaniyi Mikail Àfọ̀njá, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí SANyẹrí jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, Aderinpọ̀, olùgbéré jáde ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀wọ́n bí níyìníyì Àfọ̀njá ní ipilẹ Ọ̀yọ́, tí ó sì jẹ́ àkọ́bí ẹbí rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Micheal ní Òkè-Ibo àti Ilé-ẹ̀kọ́ ní Ilé-ẹ̀kọ́ Girama DurBar ní ìpínlẹ̀ [Oyo]] kan náà.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Alhaji Akani Olayinka parun ti won bi ni ojo kefa osu Kanl, odun 1959 ( 6-9-1959).. | wikipedia | yo |
jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré jáde àti adarí ère ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí tí ó sì dàgbà sí àdúgbò Lagos Island ní Ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Àmọ́ tí ó jẹ́ bàbá àti ìyá rẹ̀ wá láti ìlú ọ̀rọ̀ ní ìpínlẹ̀ Kwara.. | wikipedia | yo |
Oun ni oludasile Ile-ẹkọ ti o n koni ni ere onise ti won pe ni (ọdunfa Caucus) ti o kale si ilu Ebute-meta ni Ipinle Eko.ibẹrẹ Aye Kiku bi Yinka ninu ebi Yïta-ṣàgbẹ̀ ti awon obi re si je omo bibi ilu Igbo-owo ni Ipinle Kwara.. | wikipedia | yo |
LujaکC, tí ó wà ní ìdùbúmágbọ, ilé-ẹ̀kọ́ girama tí ó wà ní Ebute Olofin ní Ìpínlẹ̀ Èkó kan náà.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèréín bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré orí-ìtàgé ní ọdún 1976, òun àti ìga Olayinka àti àwọn mìíràn tí wọ́n jọ bẹ̀rẹ̀ eré nígbà náà lábẹ ilé iṣẹ́ ìkò-jáde nírí ní tí wọ́n kò lè tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ wọn mọ́.. | wikipedia | yo |
Ìyinka ti kopa ninu ere onise ori itage ti o ju Àádọ́rùún lo, ati ere Àtìgbà-dègbà olosoose ti orisirisi, amo eyi ti o gbajumọ julọ Nigunrogún.lara fiimu to ti kopalaniSọ́ọ̀lù] kopa'egbìnrìn Obahanọdún NBAkub o'ku O'e-Nigba ele-opo idajo Olalara Ọlọ́runókini ami-eye rẹàwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
ifáfitì anchor jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ Faṣiti ti aládàáni tí ó jẹ́ ti ìjọ dèéper Christian life Ministry.. | wikipedia | yo |
Ile-eko naa wa ni agbegbe kan ni Ilu Ayobo, Ipaja ni Ipinle Eko,ní orile-ede Naijiria.Awon itọkasi=.. | wikipedia | yo |
Ibojì òkú tàbíitẹ́ òkú jẹ́ ibi tí wọ́n ń sin àwọn ènìyàn tí ó ti kú tàbí papọ̀ dà sí.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀-orúkọ yìíàmì lati inú( èdè Giriki , tí ó túmọ̀ sí "Ibùsùn") tí ó túmọ̀ sí wípé ìwọnba ilé tí wọ́n yà SỌ́TỌ̀ yí ni wọ́n ṣàdáyanrí fún sin sin àwọn aláìsí si.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sábà ma ń lo àwọn gbólóhùn wọ̀nyí “ibojì òkú tàbí ìtẹ́ òkú”, amọ̀”, sá, nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì, ibojì sábà ma ń jẹ́ apá ilé kan tí wọ́n yà sọ́tọ̀ nínú ilé ìjọ́sìn láti máa fi sin àwọn àwọn paito, àlùfáà, àti dikini, ìjọ sì.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
(tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Ka-ún Ọdún 1978) jẹ́ ayàwòrán-kọ̀ròyìn ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni ayàwòrán àgbà fún Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́wọ́lọ́wọ́, Muhammadu Buhari.Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ọmọ bíbí ìlú Èkó ní Báyọ̀ ọmọboríowó.. | wikipedia | yo |
Báyọ̀ kawe gboye digírì ninu imo Applied Chemistry ni ifáfitì ti Ijoba Apapo ti o wa ni Ipinle Eko, University of Lagos.Awon Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Pastor Enoch Adejàre Adeboye, eni tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejì oṣù kẹta (Oṣù Erena) Ọdún 1942, jẹ́ òjíṣẹ́ Ọlọ́run ọmọ bíbí Ifẹ̀wàrà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni pásítọ̀-àgbà yányán àti olùdarí ijó oníràpada, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ijo ìràpadà ti Krístì (The Redeemed Christian Church of God).Igba ewe áti aáyan Ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀wọ́n bi òjíṣẹ́ Ọlọ́run àgbà yìí, Enoch Adejàre Adeboye ní ọjọ́ kejì Oṣù Kẹta ọdún 1942 ni Ifẹ̀wàrà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O kawe gboye digírì akọkọ ninu imo iṣiro/uriìkì (mathematics) ni ile eko giga ifáfitì ijoba apapo ti o wa ni ipinle Eko (The University of Lagos) l'ọ́dún 1967.. | wikipedia | yo |
Síwájú àkókò yìí, ó ti kọ́kọ́ lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Ifáfitì Nàìjíríà (The University of Nigeria, UNN) ní ìlú Nsukka ṣùgbọ́n ogun Biafra kò jẹ́ kó kàwé gboyè níbẹ̀.. | wikipedia | yo |
O fẹ aya rẹ, Fólúkẹ́ Adéníkẹ̀ẹ́ ní ọdún 1967 Bákan náà, wọ́n sì bímọ mẹ́rin.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1969, ó kàwé gboyè dìgírì kejì (master degree) nínú ìmọ̀ Ìṣòwò-San-omi àti àwọn ohun tó jọ omi (HJerusalẹmucs) láti ilé ẹ̀kọ́ gíga Ifáfitì ìpínlẹ̀ Èkó (University of Lagos) bákan ná a.. | wikipedia | yo |
Ó dara pọ̀ mọ́ ìjọ ìràpadà, The Redeemed Christian Church of God ní ọdún 1973, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ Ọlọ́run gẹ́gẹ́ bí ongbugbu fún pásítọ̀ ìjọ náà nígbà náà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ pásítọ̀ Josiah Olufemi AkinDayọ̀mi.. | wikipedia | yo |
Lọ́dún 1975, ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́, ó sì kàwé gboyè ọ̀mọ̀wé (Ph.D.) nínú àmúlò Matimatiìkì (Applied MatheJesus) láti ilé ẹ̀kọ́ gíga Ifáfitì ìpínlẹ̀ Èkó (University of Lagos) kan ná a (University of Lagos).. | wikipedia | yo |
O si tun pada gboye ojogbon (professor) ninu imo iṣiro ni ile eko giga ifáfitì Ipinle Eko (University of Lagos) ohun pelu.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Bàtà jẹ́ ohun tí ọmọ ènìyàn ma ń wọ̀ sí ẹsẹ̀ láti lè fi rìn àti láti ṣe dáàbòbò ẹ̀ṣẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìjàmbá tó lè ṣàkóbá fún ẹsẹ̀ìwúlò bàtà wọn ma ń lo bàtà yálà lásìkò ẹ̀rùn tàbí ọjọ́.. | wikipedia | yo |
wọn n lo bata lati fi ṣe iṣẹ́ èyíkéyí, ṣe eré ìdárayá, ṣe ìdáàbòbò ara àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
lai ko si bata láyé òde oni, o le sọrọ fun ọmọnìyàn lati ṣe ohunkóhun dara dara bi wọn ko ba wọ bàtà si ẹsẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Tescom ipinlẹ Eko ti o tuno si Teaching Service Commission, jẹ ajo ti o n ri si eto ìgbanisíṣẹ́ olukọ ni ipinlẹ Eko, ni o ti fìgbà kan wà labẹ iṣakoso Post- Primary Teaching Service Commission (pp– Tẹscom) pẹlu oriṣiriṣi awọn adari lati ọdun 2004 ṣaaju ki wọn to da Teachers' Estament and Penhenhen Office (te) silẹ lati ara (pp-tes) ni odun 2005, pẹlu ibamu ilana ati ofin to laa kale labẹ Isa Òfin Ofin to de eto Eko to da ẹka iṣakoso eto Eko silẹ ni ipinlẹ Eko ni ọdun 2005, ti o si fi tutor General ati permanent secretary ṣe adari fun ẹka kọọkan.Èyí waye labẹ iṣakoso Gomina Bola Ahmed Tinubu ti o ti fìgbà kan je gomina ipinlẹ Eko ri. Ajo TẹsComoju Tẹscom ni lati ma ma ṣe eto ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nipa bi a ṣe n dari, ati bi a ṣe n ṣakoso ohun gbogbo fun awọn olukọ ti ipo wọn ti to aka Heberu (Grade Level 13) ati awọn ti ipo wọn ti ju bẹẹ lọ lati ri wipe idaniloju wa wipe wọn yoo le ṣakoso, ṣàmúlò ohun ti wọn ba ni níkàá wò wọn.. | wikipedia | yo |
Igbimọ awon olukọ agba ati kekere ti won tun je oṣiṣẹ labẹ ajo yi ni wọn ma n dara ajo tescom.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Ọdẹ ni orúkọ tí a ń pe àwọn àkàndá ènìyàn kan tí wọ́n yan iṣẹ́ pípa ẹranko ìgbẹ́ ,dìde odò, pípa ẹyẹ oríṣiríṣi lọ́pọ̀ ìgbà.Ọdẹ ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí ìsẹ́ni àwùjọ Yorùbá láyé àtijọ́, ọdẹ ṣíṣe jẹ́ iṣẹ́ abiyì láàrín tí ọ̀pọ̀ àwọn òbí ma ń fẹ́ kí àwọn ọmọ wọn ò kọ́ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ àti iṣẹ́ òòjọ́.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bi ìgbàgbọ́ Yorùbá, wípé iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́, wọ́n ma ń oon ní dandan fún ara wọn láti ní iṣẹ́ lọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
Ode sise tun je ise idile awon ebi kan ti won si ma n je oruko ti o jo mo ise yi.. | wikipedia | yo |
Wọ́n á máa jẹ́ ọ̀dẹ̀jìnmí,òde,wálé òdegbémì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, àwọn ọdẹ náà tún ma ń ṣọdẹ òru léte àti dáàbò bo ìlú, èmi, àti dúkìá pátá.. | wikipedia | yo |
Àwọn irúfẹ́ ọdẹ tí ó wà ní ọwọ́ yí ni wọ́n má ń dẹ̀gbẹ́, dẹ tàkúté láti pẹran wẹ́wẹ́ àti ẹran Abijawàrà nínú igbó tàbí aginjù yálà fún títà tàbí jíjẹ. | wikipedia | yo |
Irúfẹ́ àwọn wọ̀yí ni wọ́n ma ń ṣiṣẹ́ dẹdò, Degèrè sórí alagba-lúgbú omi láti pa ẹja oriṣiriṣi yálà fún títà tàbí tàbí fún jíjẹ nínú ilẹ̀.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Omi ọ̀sà tàbí omi irọ́ jẹ́ omi Alàgbà-lúgbú tí ó dúdú lójú tàbí ní ìrísí.. | wikipedia | yo |
Omi ọ̀sà jẹ́ omi tí ẹnìkan kò mọ ibi tí ó ti ṣàn tàbí sẹ́ wá.. | wikipedia | yo |
Kò kò fẹ́rẹ̀ síbi tí omi yí kò ṣàn dé lórílẹ̀ àgbáyé.. | wikipedia | yo |
Oriṣiriṣi ẹja àti ẹran omi ló ń gbé nínú omi náà.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Paul Adefarasin ni a bi ojo karunlélógún osu kini odun 1963 je iranse Kristiẹni ati olukọ tẹlifisiọnu.. | wikipedia | yo |
House on the rock Church jẹ́ olugbalejo "The experience" orin ìhìnrereÌBẸ̀RẸ̀ AyePaul Adefarasin ni Abi ní 25 Oṣù Kíní Ọdún 1963 sí Joseph Adefarasin.. | wikipedia | yo |
Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ Giga ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lati ìlú Ìjẹ̀bú Ode, àti Hilda Adefarasin ti òjé olùgbèjà ètò àwọn obìnrin lati ìlú Èkó.. | wikipedia | yo |
Paul Adefarasin Dàgbà Ni Nigeria ati Orilẹ-ede Amerikaọmọ-iṣẹ Adefarasin lọ si Ile-iwe St Saviour ni Ikoyi ati Ilẹ̀-ẹkọ Igbobi níyàba, ni Eko.. | wikipedia | yo |
Ọkà ìwé ní Unifasiti Miami ibi tí o gba àpọ́n ti fàájì.. | wikipedia | yo |
O ṣe adase ni Florida ṣaaju ki o to pada si orilẹ-ede Naijiria.O keko ni International Bible Institute of London nibi ti o ti gba iwe-ẹkọ kan ni ile-iṣẹ Kristiẹni.atẹjade iweAdefarasin ti kọwe, iwe ti otiko ju 20 lọ awọn iwe kekere Christian iwuri ati orisun iwuri fun ọpọlọpọ.YÌÍtors.igbesi aye ara Ṣóru oṣu Keje 1995, Adefarasin Fe Ifeanyi Adefarasin, Ayaba ẹwa tẹlẹ.. | wikipedia | yo |
Odò ìṣàn ìkógosì jẹ́ ọgbà kan tí àwọn olùbẹ̀wò sí ibi ìgbafẹ́ má ń lọ láti fúnra wọn ní ìsinmi àti ìgbafẹ́.. | wikipedia | yo |
Odò iṣan ìkógòsì yí wa ní ìlú Erijiyán ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
nínú ọgbà ìgbafẹ́ yĩ, ó jẹ́ ohun ìyàlẹ́nu wípé omi Tẹ́tígun wóró àti omi tútù ti pàdé tí wọ́n kọ́ sì dira wọn lọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
Èyí mú kí kòkè ènìyàn ó fẹ́ láti máa lo gbàgàne níbi tí ó jẹ́ ayée mánigbàgbé.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ile-ẹkọ giga Crawford jẹ́ Ilé-ẹ̀kọ́ gíga aládáni ti Kristẹ́nì Apostolic Faiyh Mission.. | wikipedia | yo |
Kàn tí ó wà ní ìlú Igbẹ́, ní ìpínlẹ̀ Ìpínlẹ̀ Ògùn ní Nigeria .Wọ́n dá ilé-ẹ̀kọ́ yí sílẹ̀ ní ọdún 2005, nípa ṣe ọ̀gbẹ́ni Paul Paul Akazue, tí ó jẹ́ adarí àti ìgbà kẹta nínú iṣẹ́ ìpà ti onístolic onístolic já do ilẹ̀ Adu nígbà náà.. | wikipedia | yo |
Tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Fádèyí olóró (ní wọ́n bí ní ọjọ́ ìlọyàwó Oṣù kẹsán-an ọdún 1957) jẹ́ ọmọ bíbí gbára tàbí ní ìpínlẹ̀ Ekiti lórílẹ̀-èdè Nàíjíríàkan.Igba ewé àti aàlẹ̀ olúránlé olóró bẹ̀rẹ̀ ọdún rẹ̀ ní St.. | wikipedia | yo |
Pauls Catholic Primary School, ìgbárá odò, ni ipinle Ekiti.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ síwájú ní Timmy àgbágègé Grammar School, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ounjọ́ ṣùgbọ́n tí ó wà ni Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun báyìí.. | wikipedia | yo |
Ìràwọ̀ rẹ̀ tán nígbà tí ó kópa gẹ́gẹ́ bí Fádèyí ọlọ́rọ̀ nínú eré orí tẹlifísàn kan ní 1986 tí wọ́n pe àkọlé rẹ̀ ní àrélù.. | wikipedia | yo |
Nínú eré yìí ni orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ Fádèyí ọlọ́rọ̀ ti jẹ́ jáde.Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa adánilóró Fitu fọ̀nà Bola ele o' kú Adedógún Rúkèrúdòàwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ìjiji jẹ ilú kan ti ó lágbára púpọ̀ laarin àwọn ilú àti ilẹ̀ ọba ni ilẹ̀ Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Ìlú ìjíjíji wà ní ara àwọn ìlú ti àwọn ọmọ Yorùbá tí wọ́n kòb ní Oyo-ilẹ̀ sá sí nígbà tí ogún àwọn Àdílà kọ́ ìlú Oyo-ilẹ̀ ní ọdún 1836.Ẹni tí ó jẹ́ adarí àti alákòóso ìlú náà ní Ààrẹ Kurunmi ìjírún sí | wikipedia | yo |
Ọjà ọ̀ṣọ́di jẹ́ Ọjà ti ó wà ní apá kan ní Ìlú Ọ̀gundi ní àárín ìgboro located in Oshodi, a ṣubújá of Èkó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O jẹ ọkan lara àwọn ọja ti o tobi gidi laarin Eko.. | wikipedia | yo |
Nígbà kan rí, ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó sọ wípé àwọn ìwà búburú oríṣiríṣi bí ìlọ́ni-lọ́wọ́ gbà, olè jíjà, àpò rírẹ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Ìdí nìyí tí ìjọba fi gbé ìgbésíẹ bí wọ́n ṣe dá ọjà náà wò.. | wikipedia | yo |
Ijoba tun oja naa ko ni osu kinni odun 2016.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Ọjà Jankara jẹ́ Ọjà ti ó tóbi jùlọ ní Ìpínlẹ̀ Èkó ti wọ́n ti n ta Orissarisi ohun elo bi aṣọ, ìlẹ̀kẹ̀,Egba ọrùn, ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù karùn‐ún) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Osó ní ìpínlẹ̀ Osun lọ́lẹ̀ èdè Nàíjíríà.Igba ewé àti AÁYAN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ ipa Lama of ọmọ Yoruba 2 ti ìlú Òṣogbo, olú ìṣẹlẹ̀ Osun Osun èdè Nàìjíríà èdè Nàìjíríà | wikipedia | yo |
Ó bẹ̀rẹ̀ ìlùlù ní Baptist Secondary School ní ìlú Èkó kó tó tẹ̀ síwájú ní onígbé, The University of Ìbàdàn , ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ níbi tí ó ti kàwé gboyè dìgírì nínú iṣẹ́ tíá.Aáyán rẹ̀ nínú iṣẹ́ tíáó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tí ní 1981.. | wikipedia | yo |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa pàtàkì láti ìgbà náà.. | wikipedia | yo |
Kódà, gẹ́gẹ́ bí olùdarí sinimá àgbéléwò, òun ló darí sinimá tí wọ́n máa ń ṣe àfihàn rẹ̀ lórí ẹ̀rọ láti, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Super Story", tí gbájúmọ́ olóòtú sinimá àgbéléwò, Wale Apàdé ṣe olóòtú fún lọ́dún 2000.. | wikipedia | yo |
Bákan náà òun ló darí sinimá àgbéléwò, oh father, oh daughter" àti "This Life", gbogbo rẹ̀ lédè Gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Àìmọye sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá ni São làníyàn ti kópa gẹ́gẹ́ bi òṣèré àti adarí-sinimá.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
(tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún Oṣù Ka-ún Ọdún 1957) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí ìlú eku ní Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà .. | wikipedia | yo |
BÍ O ṣe gbajúmọ̀ nínú eré sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá, bẹ́ẹ̀ náà lọ dáńtọ́ nínú sinimá àgbéléwò èdè Gẹ̀ẹ́sì.Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀Ṣàngó (1997)Out of Bounds (1997)Owo Blow (1997)Passion of Mind (2004)Power of Sin,restless Mindtime Bello (2013)30 Days in Atlanta (2014)Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Bobìnrin Noba tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí ni ó (tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje Oṣù karùn-ún Ọdún 1980) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò àti onímọ̀ ìṣirò-owó ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Bí ó ṣe ń ṣè tíátà, bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ akorin.Igba ewé àti aákan olúwà jùbí bí olóadé sí ìlú Ikorodu ní ìpínlẹ̀ Èkó lọ́lẹ̀ èdè Nàíjíríà.. | wikipedia | yo |
Kí òô dèrò ìlú-ọba ò kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti sẹ́kọ́ndírì rẹ̀ ní ìlú Èkó.Iyanjú nídìí iṣẹ́ sinimá àgbéléwògẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ síwájú, nínálọ́wọ́ jẹ́ onímọ̀ Ìṣirò-owó, nítorí ìdí èyí, ó kọ́kọ́ ṣiṣẹ́ ní Ilé-ìfowópamọ́ gẹ́gẹ́ bí Arídìí-owó (Accountant) fún ìgbà díẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà kí ó tó dára pọ̀ mọ́ iṣẹ́ eré sinimá àgbéléwò ṣíṣe lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |