cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ìjọba ìbílẹ̀ Amuwo-Odofin ni ó tó iye ìwọ̀n 300,000, tí ó sì mú láti jẹ́ ibi tí ó gbòòrò jùlọ..
wikipedia
yo
Ninu ikaniyan ọdun 2006, wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ wípé ijọba ibilẹ Ẹnikẹ̀nimo-Odofin ni o ni iye eniyan ati olugbe ti o to 1,500,000..
wikipedia
yo
Ijoba ibile naa ni o tun pààlà pelu ijoba ibile àjérọ̀mí ati Ifelodun ni apa ila oorun, o pààlà pelu Oriade ni apa iwo Oorun, pelu Agbadarigi ni apa yànMo, ti o si tun pààlà pelu Isolo/DO ni apa ariwa.odun ibile ti won ma n se nibepupọ awon ti won je omo onile tabi onile ati omo bibi Amuwo ni won je awon eniyan Awori..
wikipedia
yo
Ìjòyè nílẹ̀ Yorùbá túmọ̀ sí àwọn ènìyàn péréte kan tí wọ́n ma ń ṣe ìṣàkóso ìjọba ìlú pẹ̀lú ọba tí ó jẹ́ aláṣẹ pátápátá lórí gbogbo ìlú àti ìgbìmọ̀ àwọn ìjòyè.Òye jíjẹ gẹ́gẹ́ bí ogún ìdíléàwọn ìjòyè kọ̀ọ̀kan ni wọ́n jẹ́ aṣojú ìdílé kọ̀ọ̀kan tí wọ́n ti jáde wá..
wikipedia
yo
Ìdílé kọ̀ọ̀kan tí ìjòyè kọ̀ọ̀kan ń ṣojú fún ni wọ́n ní ẹ̀tọ́ lábẹ́ òfin ìlú láti yan ọmọ oyè tí yóo bá ọba tukọ̀ ìlú.Orúkọ àwọn oyè patakiọ̀tún olóye ọ̀tún gẹ́gẹ́ orúkọ oyè rẹ̀ ni ó ma ń wà ní apá ọ̀tún ìtẹ́ ọba, tí yóo sì má ṣàkóso ìlú nígbà tí ọba kò bá sí nílé..
wikipedia
yo
Oye yi lo saba ma n je oye idile, Aya fi ti oba ba finu-findo yan enikan sipo yi gege bi oye idani lola nigba ti a ko ba ti ri ebi kan ti won ti n je irufèé oye bee tele.Awon itọkasiYorùbá..
wikipedia
yo
dúpẹ Jayésinmi tí yóò pé ọmọ ọdún Menilélọ́gọ́ta (62) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ bíbí Ìjẹ̀bú Ìgbò ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ṣùgbọ́n tí àwọn òbí rẹ̀ bí sí ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìgbà èwe àti aáyan Ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀dúpẹ́ bẹ̀rẹ̀ Ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ni Seventh Day Adventist Primary School ní Ilé-Ifẹ̀ , ó tẹ̀ síwájú ní Cca Commercial High School tí wọ́n ń pè ní CaC High School ní ìlú Iléṣà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun..
wikipedia
yo
Bákan náà ó lọ sí Sight & Sound International School, Ìbàdàn, lẹ́yìn èyí ó kàwé gboyè nínú iṣẹ́ Akọ̀wé Ìbàdàn Polytechnic..
wikipedia
yo
"No Rival ni àkọ́lé sinimá àgbéléwò tó mú kí ìràwọ̀ gbárù Fsinmi tàn síta..
wikipedia
yo
Láti ìgbà náà, ó ti kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Ọ̀jọ̀gbọ́n (Prof.) Suleman Elias Bogoro jẹ́ ògá àgbà (executive secretary) ti Àjọ Ìjọba Àpapọ̀ Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà fún owó ìrànwọ́ fún àwọn Ifáfitì tertiary Education Trust Fund, (Tetdíngi)..
wikipedia
yo
Ààrẹ Muhammadu Buhari yán án sípò yìí lọ́dún 2019..
wikipedia
yo
O ti wa nipo yii bakan naa lodun 2014 si 2016.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
èrìgì tàbíèégini jẹ́ àkójọpọ̀ iṣan tí ó wà lórí eegun tó gbé ẹnu dúró tí ó sì so pọ̀ mọ́ agbárí nínú làá ẹnu Louún..
wikipedia
yo
Ìṣòro ki soro to ba n doju ke èrìgì yálà látara aásan, àrùn tabi kókó buburu le ṣe àkóbá, kí o sì mú kí eniyan tabi ohun ẹlẹ́mìí tó bá ní eyín ó di aláìlera .àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ata ilẹ̀ () jẹ́ ohun ọ̀gbìn tí ó ń tinú ilẹ̀ jù tàbí jáde..
wikipedia
yo
Wọ́n ma ń lòó lọpọ̀ ìgbà fún ohun èlò ìsebẹ̀, tàbí oògùn tàbí àgbò..
wikipedia
yo
O tun jẹ ọkan lara awọn ohun ogbin ti kii tete ku ti o si ma n pe ki o to bajẹ..
wikipedia
yo
ọdọdún ni ata ilẹ̀ ma n jù lójù ibi ti wọn ba gbi si ti wọn si ti kórè rẹ̀.Ìrísí rẹ̀nígbà ti ata ilẹ̀ bá ń jù, ó ma ń ga tó ìwọ̀n mi ta kan tí ó sì ma ń ni ewé ṣooro tí ewé náà ḿ ń rí bí idà olójú méjì..
wikipedia
yo
Àwọn ewé rẹ̀ ma ń dì pọ̀ láti ilẹ̀ ni tí wọn yóo sì ya ẹ̀ka tí wọ́n bá dókè tán..
wikipedia
yo
Ewe, awo olomi aró yẹ́lò ati ẹ̀jẹ́cée ni Ewe rẹ ma n ni.Awon itọkasiàwọn ogbin..
wikipedia
yo
Lanre Adeade Hassanti gbogbo eniyan mọ si' iya Aedewérò, ti wọn ni ojo keta osu kẹwàá odun 1950, (3rd October 1950) je gbajumọ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bibi ìlú láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá ni ó máa ń ṣe jùlọ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó máa ń kópa nínú ti èdè Gẹ̀ẹ́sì náà lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
jẹ́ adura tí àwọn ẹlẹ́sìn ọmọ lẹ́yìn Jesu Kírísítì kọ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ninu Bíbélì, ninu ìwé Matiu orí kẹfa, ẹsẹ kẹsan-an títí dé kẹtala..
wikipedia
yo
nítorí ìjọba ní tirẹ̀, ati agbára, ati ògo, láyéláyé..
wikipedia
yo
Kaka Olamikan Waris jẹ́ ọ̀dọ́mọdé ọmọ ọdún mẹtala tí ó jẹ́ gbajúgbajà àfọwọ́-yàwòrán ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Waris ya àwòrán Ààrẹ orílẹ̀ èdè Faransé, Emmanuel Macron, nígbà tí ó wá sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́dún 2018 láàárín wákàtí méjì..
wikipedia
yo
Àwòrán yìí dára tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí Ààrẹ Emmanuel Macron ti orílẹ̀ èdè France fi gbà á lálejò nígbà tí ó wá sí Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Bákan náà, káká ọ̀lami Waris ló gba àmìn ẹyẹ àgbáyé akíkanjú (22nd) ní orílẹ̀-èdè Taiwan, Taiwan’s 22nd ferwọ̀nyí Global Love of Lives Award lọ́dún 2018..
wikipedia
yo
Ó pegede tí ó sin bori gbogbo adije láti gbogbo àgbáyé tí wọ́n tó 2723.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún Oṣù Karùn-ún Ọdún 1974 (5th May, 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olùdarí àti ònkọ̀tàn sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Murphy Abibi dìí olóògbé nií ọjọ́ Kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 2023 (14th May, 2023).Igba Ewe, aáyan Ìkẹ́kọ̀ọ́ àti iṣẹ́ tíátà rẹ̀wọ́n bí Aohùnbi ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ìbánisọ̀rọ̀, tíátà àti ètò nípa ṣíṣe sinimá ní ilé ìwé ire Polytechnic..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíáta lábẹ àgbà òṣèré sinimá àgbéléwò tí a mọ̀ sí Dagunro, nígbà tí ó kópa nínu sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ ìlà Olokun..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó ti ju ọgọ́ta lọ.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ireti jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó di olóògbé ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹ̀sán-án Ọdún 2002, (27th September 2002)..
wikipedia
yo
Kí ó tó di olóògbé, Ireti jẹ́ ọ̀kan lára ìlúmọ̀ọ́ká òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò, pàápàá jùlọ sinimá-àgbéléwò èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Lara awon sinima-agbelewo ti o ti gbajumo ni, ẹdunjobí, Aye awa obinrin ati opolopo awon sinima-agbelewo miiran..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ èèyàn lérò pé Rebecca Adẹ́bimpe Adekola jẹ́ ìbátan pẹ̀lú Odunlade Adekola, ògbóǹtarìgì òṣèré sinimá àgbéléwò òde òní, ṣùgbọ́n wọn kò tan rárá, orúkọ wọn kan wulẹ̀ ṣe kòńgẹ́ ni..
wikipedia
yo
Lára àwọn ọmọ Rebecca Adẹ́bimpe Adekola ní tòmíwá Adekola.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Adeṣúà etomi (ti a bi ni ọjọ kejilelogun oṣu keji ọdun 1986 tabi 1988)jẹ oṣere ọmọ orilẹ-ede Naijiria kan...
wikipedia
yo
Ní ọdún 2014, ó kópa nínu fíìmù àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "knocape on Heaven's door" èyí sì jẹ́ àkọ́kọ́ ṣe rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2016,ó gba àmì ẹ̀yẹ fún òṣèrébìnrin tí ó dára jù lọ ti Africa Magic Viewers Choice, èyí sì wáyé látipa ìkópa rẹ̀ nínú eré kan "Falling ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀Tolulope Adeṣúà ètò ètò ni a bí sí ìlú Owerri, Ìpínlẹ̀ ìmọ̀ State, ní ọjọ́ kejìlélógún Oṣù Kejì..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ajagun ẹ̀yà ẹ̀san, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Yorùbá Descent..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, ó lọ sí Queen's College, Lagos kí ó tó wa lọ sí United Kingdom ní ọdún kẹtàlá ayé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó padà gba ìwé-ẹ̀rí diploma nínú "physical Theatre, Musical Theatre and Performing Arts" ní City College Coventry ní ọdún 2004.Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn eré rẹ̀ààtò àwọn àmì ẹ̀yẹ tí ó Gbàáwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
OluBankole Wellington (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1981), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Banky w tí ó sì ń jẹ́ Banky Wellington, nínú fíìmú àgbéléwò jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òṣèré àti olóṣèlú.Ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀United States ni a bí Banky W sí, àmọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni àwọn òbí rẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó pé ọmọ ọdún márùn-ún, àwọn òbí rẹ̀ padà sí Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Láti ìgbà èwe rẹ̀ ni ó ti nífẹ̀ẹ́ sí orin kíkọ, ó bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ nínú ẹgbẹ́ àwọn akọrin ìjọ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìpínlẹ̀ Èkó ni ó ti bẹ̀rẹ̀ ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀ kí ó tó lọ sí Rensselaer Polytechnic Institute, New York tí ó ti kọ́ ọ parí..
wikipedia
yo
Ó padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2009, ó sì dá Record Label rẹ̀ sílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Awon to ko first ni Niyola, Shad, Skales and Wizkid..
wikipedia
yo
Òun sì ni ó kọ orin àkọ́kọ́ fún Etisalat Nigeria ti àkọlé rè n jẹ́ "080ẹrúsìn for Life".akojopo orin Restuou Albumsback in the building (2006)Mr..
wikipedia
yo
Chidinma 2015 cash only as featured artiste2016 made for you 2016 Onye.“oma as featured artiste 2016 mi re do (Cocoloso) feat..
wikipedia
yo
Stonebwo and Shayentààtò Awọn ami eye ti o ti gba John Letyl Song Writing Award 2006, R&B Category, For ‘My Dod' Best R&B Artiste, Nigerian Entertainment Awards 2006 Best Mamale R&B Artiste, Urban Independent Music Awards, USA, 2006 Best International Album, Nigerian Entertainment Awards 2007 for ‘Mr’ Best R R&B Video, Nigerian Music Video Awards 2008 for ‘Don’t break My Heart' Best Male Vocal performance, hip World Awards 2009 for ‘Don’t break My heart' R&B Single of the Year, 2010 hip hop World Awards for ‘Strong ting' Best R&B singer (male) and Best Music Video 2010 City People Entertainment Awardsa from awon ere rẹ Wedding Party (2016)The Wedding Party (2017 (2017)Up North (2018) Awọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Olóògbé tàbí Mathew Adekoya Okupe agbonmágbè jẹ Parakoyi oniṣowo ati ayánilówó ti ijoba fowo si..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ kan tí ọmọ rẹ̀, Doyin Òkúpè kọ lórí ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́, Facebook, òun ni olùdásílẹ̀ ilé ìfowópamọ́ ìbílẹ̀ àkọ́kọ́, ilé ìfowópamọ́ agbọ̀nmágbè agbọ̀nmágbè Bank lórílẹ̀ Nàìjíríà lọ́dún 1945..
wikipedia
yo
Oun baba to bi Doyin Okupe, gbajúmọ̀ oṣelu, Mínísítà-ana àti agbaninímọ̀ràn àgbà ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àná, Goodluck Jonathan .Ìgbésí ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ kí Olóyè Mathew Adekoya Òkúpè tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ n jẹ́ AAgbọ̀nmágbè tó di olóògbé lọ́jọ́ kìíní oṣù Kọkànlá ọdún 1984, ó jẹ́ Parakoyi oníṣòwò àti ayánilówó tí Ìjọba Àpapọ̀ fọwọ́ sí..
wikipedia
yo
Okòwò rẹ̀ tóbi débi pé ó jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká káàkiri orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Oun ni oludasile ile ifowopamo ibile akoko, agbonmágbè Bank lórílẹ̀ Naijiria lodun 1945..
wikipedia
yo
Nígbà náà, ilé ìfowópamọ́ agbọ̀nmágbè ní ẹ̀ka méje..
wikipedia
yo
Awon eka naa tedo si ebute meta, Muṣin, ifọ, Sagamu, ago-Iye, Ijebu-Igbo ati Zaria..
wikipedia
yo
Ilé ìfowópamọ́ agbọ̀nmágbè láyé ìgbà náà máa ń ya àwọn oníṣòwò ńláńlá káàkiri gbogbo àwọn ìpínlẹ̀ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́wọ́ fún okòwò wọn..
wikipedia
yo
Ile ifowopamo agbonmágbè Bank ni o wa di Ile ifowopamo wema Bank laye ode oni.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Hadiza Isma el-Rufai (ti a bi ni June 21, 1960) jẹ onkọwe ati onkọwe ọmọ ilu Naijiria, iyawo ti Gomina Ipinle Kaduna, Malam Nasir el-Rufai ..
wikipedia
yo
Hadiza da ipilẹ ti Yasmin el-Rufai Foundation (YELST), Ile-iṣẹ ti a ṣe iyasọtọ lati pese eto-ẹkọ si awọn obinrin ati awọn ọmọde, pataki kikọ ati iwadiitan-akọọlẹ el-Rufai ni a darukọ dìza Isma ni Kano, Nigeria, Nigeria si baba rẹ Mohammed Isma ati iyawo rẹ Amina iya Isma..
wikipedia
yo
O ni o ni a BSc ati MSC ni faaji (1983) ati da MBA (1992) lati Ahmadu Bello University, Zaria, ati ki o wulo Masters ni ṣẹda text (Creative kikọ) (2012) lati awọn University of Bath Spa, United Kingdom..
wikipedia
yo
láti kí ó sí lórí, tí ó bá bẹ̀rẹ̀ ṣíṣe ní kilasi University olùkọ́ni ní ẹ̀ka kọ́ni àwọn ọ̀nà (Architecture) ní Kaduna Polytechnic, àti láti iṣe lórí àwọn ẹ̀rọ ìtànná oko ní ìsàlẹ̀ (àwọn National Elecriatric Power Authority, Nepa), nípa tazama aba Olómìnira..
wikipedia
yo
Lẹhinna o di minisita ile-ilu olu-ilu ati Gomina ti Ipinle Kaduna .Ise agbese kikọ ni ọdun 2017, El-Rufai ṣe atẹjade iwe rẹ an abundance of Scorpions (A iwe Ouida)..
wikipedia
yo
ìjẹ́rìsí ti Nobel, láti èyítí a ṣe ìwúrí àwòkọ́ṣe látiíṣe ìṣáájú ní ibi ìtọ́jú aláìníbaba ní olú-ìlú Àbújá, àtipèé ọmọ náà kọ̀wé lórí àwọn aláìníbaba..
wikipedia
yo
Ìwénaa ni a gbekalẹ n Ake Arts ati Book Festival of 2017..
wikipedia
yo
Helon Abel ṣapejuwe iiṣẹ́ẹ ònkòwé, “ itan itanjẹ pipadanu ati ibanujẹ lori agbara ati ifaramo obirin ” (ni Gẹẹsi, “itan itan pipadanu ati itan akin ti agbara ati ipinnu obirin” ). paapo pẹlu ọkọ rẹ, el-Rufai da ipilẹ ti Yamin El-Rufai Foundation (ye) ni ọdun 2013 lati ṣe iranti ọmọbirin rẹ ti o ku ni ile rẹ ni Ilu Lọndọnu ọdun 2011..
wikipedia
yo
Ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí a dá ní ọdún 2017 pẹ̀lú èrò tí kọ́ni àwọn ọmọdé lórí ẹ̀dá, “Ní pàtàkì àwọn ọmọbìrin, láàrín àwọn ọjọ́-orí 8 sí 19", àti àwọn obìnrin tí ó dàgbàsókè, nípasẹ̀ àfikún ti “àwọn ọjà.” Àti àwọn olùkọ́ni àti àwọn ìwé tí ó nílò kíkà díẹ̀ síi..
wikipedia
yo
“ Ni idahun si Awọn iya-ile ti Ipinle Kaduna, o tẹsiwaju lati lo ọfiisi rẹ ni awọn okunfa alanu ati ni iranlọwọ awọn aláìlera, ni ipese oogun si awọn alaisan ti o ni ẹjẹ ni ati ni ayika Kaduna.awọn alakoso..
wikipedia
yo
jẹ́ ilé ìfowópamọ́ ìbílẹ̀ àkọ́kọ́ lọ́lé èdè Nàíjíríà ti ìjọba àpapọ̀ fún ṣò..
wikipedia
yo
Oloye Mathew Adekoya Okupe agbonmágbè ni o da a sile lodun 1945..
wikipedia
yo
Ile ifowopamo agbonmágbè lo wa di Wema Bank ti ode oni.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ile ifowopamo wema je okan ninu awon ile ifowopamo to lowolowo julo ti ijoba apapo orile ede Naijiria fun ni iwe ase lati le sise bere ede Naijiria..
wikipedia
yo
Parakoyi onisowo aje ọjọ́un, Oloye Adekoya Okupe agbonmágbè ló dáa sílẹ̀ lodun 1945..
wikipedia
yo
agbọ̀nmágbè Bank ní orúkọ tí ó sọ ọ́ nígbà náà, ṣùgbọ́n àyípadà àti àtúnṣe ló sọ ọ́ di Wema Bank.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Doyin Okupe jẹ́ olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀ èdè Nàíjírìa..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ àgbà àná lórí ìbáṣepọ̀ àwọn ará ilú fún ààrẹ àna orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Goodluck Jonathan lati ọdún 2010 sí 2015..
wikipedia
yo
Kí ó tó bá Goodluck Jonathan ṣíṣe, ààrẹ àná, Olusegun Obasanjo yan án lọ́dún 2003 gẹ́gẹ́ bí agbẹnusọ rẹ̀..
wikipedia
yo
O ti fìgbà kan dije dupò fun gomina ipinlẹ Ogun Labẹ Aásìya People's Democratic Partyawọn itọkasi..
wikipedia
yo
Asat lamina ọ̀ṣọ́àlà Mon tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù Kẹwàá ọdún (9 October 1994) jẹ́ agbábọ́ọ̀lùbìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó ń gbá bọ́ọ̀lù jẹun fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lùbìnrin Barcelona ní orílẹ̀ èdè Spain..
wikipedia
yo
Ó máa ń gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ agbábọ́ọ̀lù-ẹ̀rí, (Striker).àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù Kẹta ọdún 1957 jẹ́ Ọ̀gágun àti olórí ogun àṣírí orílẹ̀ ède ìye láti ọdún 1998 títí di ọdún 2020 tí àwọn ọmọ ogun orílẹ̀ ède Amẹ́ríkà pa á..
wikipedia
yo
Oun ni olori ogun The Islamic Revolutityl Guard Corps (Ir2C) lórílẹ̀ èdè Iran..
wikipedia
yo
Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, Ikú Qàkọsílẹ̀Canterbury Soímánì ti fa ìbẹ̀rù-bojo sí gbogbo àgbáyé láti ìlérí àti ìrọ́kẹ̀kẹ̀ ogun ti orílẹ̀ èdè Iran àti Amẹ́ríkà ń pè sí ara wọn..
wikipedia
yo
Èrò ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni wípé, bí àjọ àgbáyé, United Nations kò bá tètè pẹ̀tù pípẹ́ náà, ó lè dogun àgbáyé kẹ́ta..
wikipedia
yo
Lórí ikú Qàkọsílẹ̀m Soganmani, orílẹ̀ ède Amẹ́ríkà àti ìgba gbé nígi ìgbò ìgé.àwọn Ìtọ́kasíàwọn ènìyàn ará ìnín )
wikipedia
yo
Jẹ́ ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́ lórí afẹ́fẹ́ ẹ̀rọ ayélujára..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ìkànnì ti lè ní àǹfààní sí láti orí fóònù alágbéká, ẹ̀rọ kọ̀mpútà tabili àti ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà agbelọ́wọ́ tí ó ní àmúmọ́ láti já lu ayé lórí afẹ́fẹ́..
wikipedia
yo
Ilé iṣẹ́ tí ó ń ṣe kòkárí rẹ̀ gúnwà sí Menlo Park, California, lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Ọ̀gbẹ́ni Mark Zuckerberg ni ó ṣẹ̀dá rẹ̀ lọ́dún 2004..
wikipedia
yo
Àlèfi Facebook fọ̀rọ̀ ránṣẹ́ sí olumulo Facebook míràn, a sì tún le fi Facebook fi fọ́tò àti fídíò ránṣẹ́ sáwọn ọrẹ wa.Ka eleyĩ náà WhatsAppÀwọn Ìtọ́kasíInternet ..
wikipedia
yo
Mark Elliot Zuckerberg tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá osu karun-un ọdún 1984 (14 May 1984) jẹ́ oníṣòwò ayélujára, àfọwọ́ṣàánú àti ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ àti aláṣẹ yànana ìkànnì abadọrẹ̀ẹ, Facebook ọmọ orílẹ̀ Èdè Amẹ́ríkà.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ará Ameriseewon onisowo ara Amerika..
wikipedia
yo
Jáwọ́ tàbí ìgbànú jẹ́ àpò ìpawọ́ sí ti àwọn ìyá-lọ́jà àti baba-lọ́jà ma ń so mọ́ inú tí wọn yóò daṣọ bò lásìkò tí wọ́n bá ń tajà lọ́wọ́.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Àmọ̀tẹ́kùn jẹ́ ẹ̀ṣọ́ àsọlùú tí àwọn gómìnà mẹ́fà tí ó wà ní ilẹ̀ Yorùbá ṣẹ̀ṣẹ̀ dá sílẹ̀ lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kìíní ọdún 2020 (9th January 2020) láti kún ìjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ láti mójú tó ètò ààbò gbogbo ilẹ̀ Káàárọ̀-ó-jíire tí ó dàbí pé ó ń mẹ́hẹ..
wikipedia
yo
Àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ mẹ́fẹ̀ẹ̀fà tó wa ilẹ̀ Yorùbá fi èso àmọ̀tẹ́kùn lọ́lẹ̀ ní ìlú Ìbàdàn, tí ń ṣe olú-ìlú ilẹ̀ Oòduà.Iṣẹ́ àwọn ẹ̀ṣọ́ àmọ̀tẹ́kùn àwọn gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Èkó, Ọ̀ṣun, Èkìtì, Ondó àti Ògùn ni wọ́n parapọ̀ tí wọ́n sìn dá ẹ̀sọ́ ààbò yìí sílẹ̀ láti bẹ̀rẹ̀ sí ní dá ààbò gbogbo ènìyàn àti ilẹ̀ Yorùbá pátápátá..
wikipedia
yo