cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Apata Memorial High School ni ó ti gba eto-ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti èyí tó tẹ̀le..
wikipedia
yo
Fásitì ti ìjọba àpapọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó ni ó ti gboyè Bachelor of Education,Àtòjọ àwọn orin rẹ̀orin tí ó dá kọààtò àwọn àmì ẹ̀yẹ tí ó ti Gbàáwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Vlado Goreski (1958) jẹ oṣere ara Makedonia, oluṣeto ipele.O pari ile-iwe giga ti ile-iwe Fine Arts ni Ljubljana, Slovenia,,o,.o jẹ oludari aworan ti International Graphic Trienmon - Bitola..
wikipedia
yo
Orce James tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ Oṣù kejìlá Ọdún 1999 (American December 1999) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ṣíṣe ọmọ bíbí orílẹ̀ ède gẹ̀ẹ́sì Is Footballer tí ó máa ń gba àyè ìàbòsókè bo Ojúlé fún Ikọ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Chelsea f.C..àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Eyi ni atojo oruko awon agbaboolu afẹsẹgba idije agbabuta orile-ede Geesi ti won ti kopa ninu idije agbabuta boolu afẹsẹgba ti orile ede geesi fun igba ọọdunrun tabi ju bee.Àtòjọ oruko awon agbaboolu afẹsẹgba idije agbabuta orile-ede Geesia se atojo yii nipa wiwo iye igba ti agbaboolu afẹsẹgba kopa..
wikipedia
yo
Bí èyí bá dọ́gba láàrín agbábọ́ọ̀lù méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, àtòjọ yìí yóò wá wáyé nípa wíwo ọdún tí wọ́n kọ́kọ́ kópa nínú ìdíje náà, bí èyí bá tún dọ́gba, àtòjọ yóò wáyé nípa àtọ̀ álúfábẹ́ẹ̀tì tí ó bẹ̀rẹ̀ orúkọ wọn..
wikipedia
yo
Àtúnse lórí àtọ̀ yìí wáyé kẹ́yìn lọ́jọ́ kejìlá oṣù kìíní ọdún 2020..
wikipedia
yo
Arsenal football Club jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ àgbàlé-àfẹsẹ̀gbá ṣiṣẹ́ tí ó fìkàlẹ̀ sí ìlú Islington ní London lórílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, tí ó n díje nínú ìdíje àgbàbúta bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì, ìdíje bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá tí ó ga jùlọ lórílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá yìí ti gba ife-ẹ̀yẹ mẹtala ninu ìdíje àgbàbuta bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀ ède gẹ̀ẹ́sì, bẹ́ẹ̀ náà ni ó gba ìfẹ́ ẹ̀yẹ FA Cup mẹ́tàlá àti àwọn àṣeyọrí mìíràn nínú ìdíje bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá..
wikipedia
yo
Je iko egbe agbaboolu afẹsẹgba akoko lati apa guusu orile ede Geesi lati darapo mo idije agbata boolu-afẹsẹgba ti orile ede Geesi lodun 1893, won sin tun je ipo keji ninu awon iko to pegede ninu awon egbe agbaboolu afẹsẹgba gbe ko gbe ede Geesi..
wikipedia
yo
gba ife ẹ̀yẹ márùn-ún, àti àwọn ife ẹ̀yẹ mìíràn tó tó márùn-ún..
wikipedia
yo
Leyin naa, opolopo Ife eye, paapaa ju lo idije agbata boolu-afẹsẹgba ti orile ede geesi.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ti ògbufọ̀ rẹ lédè Gẹ̀ẹ́sì jẹ́ English Premier League, EPl jẹ́ ìdíje bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ti o ga julọ lórílẹ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ìkọ́ ẹgbẹ́ agbabọọlu afẹsẹgba okòó (20) maa n dije fun lọdọọdun..
wikipedia
yo
O jẹ okowo pataki lorilẹ ede Gẹẹsi ti gbogbo iko egbe agbabọọlu afẹsẹgba ni ipin-idokowo..
wikipedia
yo
Ìdíje yìí máa ń bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹjọ, ó sì máa ń parí ní oṣù karùn-ún ọdún tó tẹ̀ lé..
wikipedia
yo
Odidi ifẹsẹwọnsẹ mejidinlogoji lo maa n waye laarin awọn iko ẹgbẹ agbabọọlu afẹsẹgba okòó..
wikipedia
yo
Lọ́pọ̀ ìgbà, ọjọ́ Àbámẹ́ta àti ọjọ́ Àìkú ni ifẹsẹwọnsẹ láàárín àwọn ikọ̀ ẹgbẹ́ agbabọọlu afẹsẹgba wọnyi máa ń wáyé..
wikipedia
yo
ṣùgbọn nígbà mìíràn, O máa n wáyé láwọn ọjọ mìíràn..
wikipedia
yo
Pigke owo ile okere ni won maa n ri ninu idije yii, paapaa julo ninu iṣafihan rẹ lori ero tẹlifísàn kaakiri gbogbo agbaye..
wikipedia
yo
The deal was worth ps1 billion a year domestically as of 2013-14, with sky and Kéde group securing the Domestic Rights to Broadcast 116 and 38 Games Aláyọ̀ctivelyàwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
obarisi Ovie Omo-Agege ti won bi ni ojo ketalelogun osu kejo odun 1953 (23rd August 1953) je amofin, oloselu omo bibi ipinle Delta lori ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni Igbakeji-Aare ile Igbimọ Asofin agba ti orile ede Naijiria ati asoju agbegbe aarin Delta ni ile igbimo asofin laarin odun 2015 si 2023..
wikipedia
yo
wọ́n dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bí igbákejì ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti Nàìjíríà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress(APC), lọ́jọ́ kọkànlá oṣù kẹfà ọdún 2019 nígbà tí ó borí alátakò rẹ̀, iké Ekwèrèiparun, ti ẹgbẹ́ Òṣèlú People's Democratic Party, PDP..
wikipedia
yo
Omo-Agege ni aṣofin agba akọkọ lati Ipinle Delta ti o dórí oye oṣelu yii.otun le kaStella Oduah-ògìwwọnyiawon itọkasiawọn oloselu ara Naijiria..
wikipedia
yo
Omawumi Megbélé (ti a bi ni ojo ketala, osu kerin odun 1982), ti a mo si Omawumi jẹ olorin orile-ede Naijiria, akọrin sile ati osere ti ẹya yínyínkiri..
wikipedia
yo
O jẹ Brand Ambassador fun Globacom,, kọ̀nga.com, ati Malta Guinness..
wikipedia
yo
Ó dara pọ̀ mọ́ Kampáínì kan tí ń jẹ́ “látàrí with the Energy of Africa” 🙂
wikipedia
yo
Ní ọdún 2007 tí ó kópa nínu West African Iidols tí ó sì yege pẹ̀lú ipò kìíní ní àwọn ÈÈYÀN bẹ̀rẹ̀ sí ní mọ̀ ọ́..
wikipedia
yo
Album rẹ̀ the LASRI of Truth tí ó kòá ṣe já sí àyọrí ńlá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìgbésí ayé rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rea-ẹ̀kọ́ bí Omawumi sínú ìdílé Chief Dr..
wikipedia
yo
Ó lọ sí Nana Primary School nígbà tí ó wà ní kékeré, kí ó tó wá lọ sí College of Education Pegbèmueller Secondary School..
wikipedia
yo
Ó lọ sí Ambrose Alli University ó sì jáde pẹ̀lú degree nínú law..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga ní ọdún 2005, ó kó lọ sí ìlú Port Harcourt ní Ìpínlẹ̀ Rivers State, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ amòfin "O.S Megbele & Associates" ti ẹbí rẹ̀..
wikipedia
yo
O tun lọ si Alliance française nibi ti o ti gboye ninu French..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹtàlá, Oṣù Kìíní ọdún 2018, Toyin Yusuf gbé e níyàwóO.ààtò àwọn àmì ẹ̀yẹ tí ó Gbàáwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Dojúaljirin jẹ ilana Ìkẹ́kọ̀ọ́ ti Awọn ara Ile Hausa ni orile-ede Naijiria n lo lati ko awon omo won lẹ́kọ̀ọ́ esin Islam..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe Afayọ orúkọ ìlànà ìrụ̀ yí láti ara ọ̀rọ̀ máyì "Al-Sji" tí ó túmọ̀ sí "A rin rin-ajo"Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀ láyè àtiwọ́n bẹ̀rẹ̀ ìlànà ìlànà yì yí ìlú kanem, níbi tí pupo nínú àwọn adari wọn jẹ́ onímọ̀ nípa oníránìbéránì tí ó jẹ́ ìwé òmọ̀ ẹ̀sìn Islam..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ọgọrin mẹrin ọdún ó dín mẹwa (700), tí wọ́n dá ìlú ṣòkòtò sílẹ̀ ni wọ́n oon ní dandan lati máa lo ìlànà ikẹkọ ẹ̀sìn Islam..
wikipedia
yo
Àwọn Ọba ilẹ̀ Sokoto àti Borno ni wọ́n wa n ṣakoso Eko Al-ṣọ́un..
wikipedia
yo
Lásìkò yí, àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ ma ń wà lọ́dọ̀ àwọn òbí wọn ni, ti àwọn ilé-ẹ̀kọ́ wọn gbogbo sì wà ní ìtòsí ìletò wọn gbogbo..
wikipedia
yo
Àwọn olùbẹ̀wò aṣojú ọba sì ma wá ń ṣèbẹ̀wò, tí wọ́n sì ń jábọ̀ fún ọba..
wikipedia
yo
Awon ile-eko wonyi ni o je wipe owo apo ilu, obi, ọrẹ àtinúwá (ṣàdá (QAhq) , owo ori (zt) ni won fi n toju ile-eko naa.D]rin aye ode wura odun 1904, ayipada de ba eto eko Almajirin nigba ti awon Geesi fi agbara wo ile Hausa ti wonnsi fipa lowo lowo awon Emir..
wikipedia
yo
Fífipá gbàjọba yí mú kí àwọn Gẹ̀ẹ́sì ó pa ọ̀pọ̀ nínú àwọn Emir, tì púpọ̀ wọ́n sí pàdánù ìjọba ilé won sí owó àwọn Gẹ̀ẹ́sì, fún èyí ètò ẹ̀kọ́ Gilèpojì kó rí ìtọ́jú tó péye mọ́.. Mo
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, wọ́n dá Boko sílẹ̀, tí ó dásẹ̀ sí "Ìmọ̀ ẹ̀kọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì”
wikipedia
yo
Ijoba tuntun fopin si inawo si eto Eko Almaji lati apo ijoba ti ko si si ìrànwọ́ kankan mọ fun eto ẹkọ Taori Mox..
wikipedia
yo
Eyi ni ó mú ki àwọn olukọ àti akẹ́kòọ́ ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gba bàrà láti fi jẹun.Àwọn ìtọ́kaṣii..
wikipedia
yo
Odò ni ohun-elo ile ìdáná kan ti a ma n sábàá lo lati fi lo ata, gun ẹ̀wà, èlùbọ́ iyan ati bẹẹ bẹẹ lọ nipa fifi ọmọ odó gún wọn po titi yoo fi ri bi a ti n fẹ.irisi rẹodo () ti a n wi yi ni irisi rẹ da bi igba róbótó.Ohun ti wọn fi n ṣe odòwọn ma n se ọdọ lati ara ako igi, Irin,Sera, tabi akọ okuta bi àpáwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Ata ni ohun èso ti a ka ti a si fi pèsè yálà ohun jíjẹ bí ọbẹ̀ tabi mimu mìíràn ki ó lè ta lẹ́nu kí ó sì lè ṣe anfani fún ara..
wikipedia
yo
Ppaa paa julo lasiko otutu tabi ọ̀gìnìntìn.Ori ata to waata rodoata Galu gbigbeata ileata tatase timo ati bee bee lo.Awon itọkasiàwọn ogbinàwọn ohun ogbin jíjẹ..
wikipedia
yo
Tajudeen Oyewole tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ábíjà ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹ̀wá , Ọdún 1957.jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá àgbéléwò, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O saba ma n kopa ninu ere sinima gege bi ògbójú babaláwo ati onisegun to gbọ̀nà ti o si ma n fi agbara rẹ gba awon eniyan sile ninu ere.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Faláṣẹ Olabankẹwin tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Dagunro jẹ́ òṣèré Ori ìtàgé oun sinimá àgbéléwò,ọmọ bíbí ìlú Òṣogbo ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn sinimá tí ó ti ṣe funfunka kí'le Ku'2008)Inúnibíni (2007)Ìkìlọ̀ Agba (2008)àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Ikú Rése Wole sí olóògbé ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Kẹfà Ọdún 2019..
wikipedia
yo
Benedict Peters jẹ́ olówó Billionaire, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ile ise ti o nise pelu ise epo robi ti o je ti Adani ti o si tobi julo ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ni nkan bi osu kokanla odun 2014, Benedict ti ni to iye owó tí ó tó bilionu méjì ó lé owó méje dọ́là ($2.7 billion), gẹ́gẹ́ bí owó ara eni òun ni ó wà nípò keje gégé bí ẹni tí ó lówó jùlọ nílée Adúláwọ̀, gẹ́gẹ́ bí àjọ Ventures Africa ṣe toô sí..
wikipedia
yo
"The Richest people in Africa" .Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹpẹtẹrs jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Delta, tí wọ́n sì bí ní ìlú Abakaliki, ní ní ìpínlẹ̀ Ebonyi, sí inú ẹbí onísẹ́ ilé ìfowópamọ́..
wikipedia
yo
Ó lọ sílé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti ​ èkùlù ní ÌlúEnugu, tí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ oniwe mẹ́wàá ti Federal Government College Enugu, tí ó sì tẹ̀ síwájú ni after which he pro proeeded to Fásitì Benin, níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí dìgírì (B.Sc) nínú ìmọ̀ jọ́gíráfì àti ìfẹ̀tọ́ sí àwùjọ (Geography and Town Planning). Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí elépo rọ̀bìo bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní inèrè ọdún 1990, nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Ocean Oil tí ó yí padà sí Oan dòd Nigeria lọ́wọ́d, iyán àwọn bí Adéwálé Tinúbú, Mofe Báyọ̀ àti ọ̀nàjíte Okoe-
wikipedia
yo
ó tún bá ilé-iṣẹ́ Mrs Oil Nigeria PLC ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí adarí àgbà, saájú kí ó tó kúrò lọ dá ilé-iṣẹ́ Sigmund CommunECci sílẹ̀ ní ọdún 1999..
wikipedia
yo
.O da ile-iṣẹ aite sile ni odun 2008, eyi ti o je eka eka Sigmund communci Ìtọ́kasí.Awon ìtọ́kasígbo in AFRI Ara Naijiria..
wikipedia
yo
Ọbẹ̀ ni ohun jijẹ ti a fi oriṣiriṣi ohun èlò ìsebẹ̀ pèsè, lati fi jẹun Láje gbadun..
wikipedia
yo
Ọbẹ̀ ni ò ṣéé jẹ ní gbígbóná tabi kí ó lọ́ wọ́ọ́rọ́, a sì lè jẹ̀ẹ́ ní tútù pẹ̀lú.Àwọn èròjà òBẹlilọ èròjà ọbẹ̀ dá lórí irúfẹ́ ọbẹ̀ tí a bá fẹ́ sè..
wikipedia
yo
Ọbẹ̀ ṣíṣe dá lórí bí ilú tàbí àwọn ènìyàn ibẹ̀ bá ṣe gbáfẹ́ nípa ońjẹ sì ni..
wikipedia
yo
Ìjàpá jẹ́ ẹranko ti ó máa ń gbé nínú omi, tàbí ìyàngbẹ ilẹ̀..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ẹranko tó ní ọgbọ́n tí ó fi ń dá ààbò bo ara rẹ̀..
wikipedia
yo
Ìjàpá le wà láàyè fún ọgọrin si àádóje ọdún.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ẹranko afàyàfà..
wikipedia
yo
Ata rodo () jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ewébẹ̀ tí ó ṣe pàtàkì nínú ohun èlò ìsebẹ̀ jákè-jádò orílẹ̀ àgbáyé..
wikipedia
yo
Àwọn èròjà yí ni wọ́n wúlò fún mímu ìrora kúrò fúni, tí ó sì ma ń jẹ́ kí kẹ̀lẹ̀bẹ̀ ó dúró ní ihò tàbí káà imú àti káà ọ̀fun..
wikipedia
yo
Ata rodo tún ń sẹ́kúnlápá fún àwọn ọmọ ogun ara kí wọ́n lè lágbára sí..
wikipedia
yo
ti ta ata rodo ni ó tún ma ń jẹ́ kí ẹ̀fọ́rí òun kátà ó fi àgbàọ́ ara sílẹ̀, kódà tó fi mọ́ àìsàn aromọléegun, àti àwọn àìsàn mìíràn.Bí wọ́n ṣe ń jata roté orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, kò fi bẹ́ẹ̀ sí ońjẹ kan tí a lè se láí sí ata rodo.A le lòó mọ́ àwọn èròjà ọbẹ̀ tókù, a le lòó lásán kí a fi ṣe kúrú, a lé jẹ sí jẹ́ lásán a sì lè fi ṣe ohun kạfí tó bá wù wa.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ọ̀gbìn..
wikipedia
yo
Ata ṣọmbọ ni wọ́n ma ń lò láti lè jẹ kí ońjẹ ó ta lẹ́nu..
wikipedia
yo
Èròjà (Capsaicin) ni o ma ń fun ata ṣọmbọ ní agbára lati ṣe iṣẹ́ tita lẹ́nu.Ibi tí 28 ti ṣe waata 28 ló ni ó ṣẹ̀ wá láti orílẹ̀-èdè Mẹ́síkò ..
wikipedia
yo
Ata ṣọmbọ ló tàn kálẹ̀ àgbáyé láti ilẹ̀ Mẹ́síkò látàrí Idowọ́pọ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n maa ń lò ó fún ìrésí ṣiṣẹ́ àti oògùn ìbílẹ̀.àwọn ìtọ́pọ̀ àwọn ogbin..
wikipedia
yo
Ata tatase kìí sábà ta ni tirẹ̀, nítorí wípé ó ma ń dùn ni tirẹ̀..
wikipedia
yo
Agbegbe ti ata yi ti feran julọ lati maa dagba ai ni ibi ti o ba lo woro bi iwọn .Awon itọkasi awọn ogbin..
wikipedia
yo
tìtì jẹ́ èèè ìréfẹ́ àti ohun ogbin tí a lè jẹ́ lásán, tàbí kí a òloo pọ̀ mọ́ àwọn èròjà kí tí kù bí ata rodoata sóríata gbiata gbiata òṣẹ òṣẹ̀ tí tìtì tìmọ̀ tì dá lórí abẹ́lẹ̀ tí a bá fẹ́ tí tí tí a bá fi èròjà yí èròjà yí kuń àwọn ẹbu òkan tókù, yoo mu kí Ọba náà náà ní ìràyàn tó peregedé..
wikipedia
yo
The Species Egtedted in Western South America and Central America.Bí a ṣe ń jẹ́ tímọ́ ma ń lo tìmọ́ ní oríṣiríṣi ọ̀nà bí kí a fi a jẹ ní tútù tàbí kí a ṣeé lọbẹ, a lè fi ṣe ọ̀d Salad, wọ́n sì tún ma ń fi ṣe ohun mímu Elé-Dàda.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Helen Paul jẹ́ aláwàdà, olórin àti òṣèré orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O tun maa n sise ipanile-in re lori eto "stand Up Nigeria", Tatafo si ni a mo si lori lori itage..
wikipedia
yo
Ohun tó yà á sọ́tọ̀ ni ohùn rẹ̀ tí ó dà bí ti ọmọdé birin tí ó máa ń lọ láti fi Panlẹ́rìn-alòdìsí.Àìpẹ́ yìí ni ó gboyè doctorate nínú Theater arts láti Yunifásítì ìlú-Èkó-Èkó University of Lagos.Iṣẹ́ RePaul ti ṣiṣẹ́ ìgbéto sáfẹ́fẹ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé-iṣẹ́ ìgbéto sáfẹ́fẹ́ bíi Lagos Television (LTV 8),Continental Broadcasting Service (CBS), àti MNET (nibi tí ó ti jùmọ̀ pẹ̀lú àwọn mìíràn gbé ètò jara sí orí Africa Magic) ní Nàìjíríà.Ó di gbajúmọ̀ láti ṣíṣàwàdà rẹ̀ lórí ètò orí rédíò Wetin Dey lórí Rédíò Continental 102.3FM ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Àwọn èèyàn mọ̀ ọ́ sí “Tata” lórí ètò orí rédíò náà.Iṣẹ́ orin kíkọ rẹni oṣù keje ọdún 2012, ó gbé orin rẹ̀ Welcome Partyjáde..
wikipedia
yo
Àwọn orin Afro-Pop bíi "boju bojú", "Comtercular", "gbẹ̀du", "God foràpẹẹrẹ", Orin Afro rnb "Children of the World" ati "Use Calculator(orin Eko kan nipa HIV/AIDS)" wà ninu àwo orin naa..
wikipedia
yo
Ó jẹ èso tí ó wúlò lọ́pọ̀lọpọ̀, pàápàá jùlọ fún jíjẹ, ìwòsàn ṣíṣe, adi-agbọ̀n àti àwọn ohun èlò mìíràn tí wọ́n máa ń fi àgbọn ṣe.Ìwúlò agbọ̀noríṣiríṣi nǹkan ni àgbọn wúlò fún..
wikipedia
yo
Bí wọ́n ṣe ń jẹ agbọ̀n bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ń fi í ṣe oríṣiríṣi nǹkan mìíràn.Agbọ̀n wà fún jíjẹ́ènìyàn lè jẹ́ funfun inú èso àgbọn tí ó bá gbó kàkà..
wikipedia
yo
Kódà, àwọn mìíràn máa ń jẹ funfun inú èso àgbọn tí kò gbó..
wikipedia
yo
Ní jíjẹ, a máa ń fi agbọ̀n mú gàárì, wọ́n ń fi àgbọn ṣe ìrẹsì (Coconut Rice) àti àwọn oúnjẹ mìíràn.Adi àgbọ́nadi agbọ̀n jẹ epo tí wọ́n máa ń sè láti ara funfun inú èso àgbọn..
wikipedia
yo
A lè fi adi-agbọ̀n ṣe ọbẹ̀, a lè fi jẹ iṣu, kókó, gbátara ṣíṣe àti àwọn oúnjẹ mìíràn..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń fi adi-agbọ̀n ṣe ọṣẹ àti àwọn ohun èlò mìíràn.Ìwọ-wádìí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ fihàn pé ẹgbẹlẹmùkù ìwòsàn ni wọ́n lè fi àgbọn ṣe.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìwà àjẹbánu jẹ́ abala ìwà àìṣòdodo tàbí ìwà ọ̀daràn ti àwọn aláṣẹ ilẹ̀ iṣẹ́, àwọn òṣèlú tó wà nípò àṣẹ tàbí agbára máa ń hù fún àǹfàní ara wọn..
wikipedia
yo
Lára àwọn ìwà àjẹbánu ni ẹ̀gúnjẹ gbígbá, ìwà ìkówójẹ nípò àṣẹ, ìṣègbè fún ẹbí, ara tàbí ọ̀rẹ́ ẹni fún àǹfàní láìtẹ̀lé ìlànà tàbí òfin..
wikipedia
yo
Ó lè wáyé níbi iṣẹ́ kéréje ṣùgbọ́n èyí tí ó bá wáyé láàárín àwọn olóṣèlú tàbí àwọn tó wà nípò àṣẹ jẹ́ èyí tí ó gbajúmọ̀ jùlọ..
wikipedia
yo
Bi o tilẹ wu ki o kere to, ohun ti ko dara, ko lorukọ meji.Awọn itọkasiijọba..
wikipedia
yo
Tàbí ẹ̀gúnjẹ ní gbígba owó tàbí ẹ̀bùn mìíràn lọ́nà àìtọ́ láti ṣègbé fúnni fún èyíkéyìí ànfãní..
wikipedia
yo
Àwọn ọ̀gá ilé-iṣẹ́, àwọn olórí, aláṣẹ tàbí àwọn olóṣèlú ní àjẹ́ ìwà ìbàjẹ́ yìí ṣáábà máa ń ṣe lórí jùlọ..
wikipedia
yo
Àwọn àwọn adájọ́, ọlọ́pàá àti àwọn agbófinró mìíràn a máa gba ẹ̀gúnjẹ láti ṣègbé fún ọ̀daràn tàbí láti gbẹ̀bí fún aláre..
wikipedia
yo
Ọwọ́-ẹ̀yìn, tí a tún lè pè ní owó-àbẹ̀tẹ́lẹ̀ tún máa ń wáyé àwọn ilé ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Awon oluko miiran a maa ẹ̀gúnjẹ lati fún akekoo ni Máàkì tabi fun un ni esi ibeere idanwo.Awon itọkasiiwa..
wikipedia
yo
Ewúro tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan lára ẹbí AsTẹrapeculiarities, jẹ́ ewébẹ̀ tí ó wọ́pọ̀ jù lọ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀.Ìrísí rẹ̀Igi Ewúro máa ń ga nílé tó iye bàtá ..
wikipedia
yo
Tí ewé rẹ̀ sì máa ń gùn tó níye, ẹ̀yin èwe náà kò sì dán mọ́rán..Àwọn orúkọ tó ń jẹewúro ni wọ́n maa ń pè ní Bitter leaf ní èdè Gẹ̀ẹ́sì, nítorí adùn kíkorò tó ní..
wikipedia
yo
Wọ́n maa ń pè ní Grawa ní èdè Amharic, etídòt ní èdè Ibibio, Onugbù ní èdè Igbo, Ity ní èdè Tiv, Oririwo ní èdè Edo, àwọnwọnó ní èdè Akan, Sobaka/Chu dókì ní èdè Hausa, Mulùlùz ní èdè Luganda, Labrí ní èdè ACholi, Olusia ní èdè Luo, àti NdoLeh ní orílẹ̀-èdè Cameroon.Ìwúlò ewufun IPbùfun ọbẹ̀ maa ń fi ń fi ọbẹ̀ ṣe nígbà tí wọ́n bá ti gbo tí gbó ìfiẹ̀yàn inú rẹ̀ kúrò pẹ̀lú iyọ̀ àti epo pupa..
wikipedia
yo
Wọ́n lè fi ṣe ọbẹ̀, tàbí kí wọ́n ṣeé pò mọ́ àṣàrò iṣu tàbí òmíràn.Fún ìwòsànwọ́n máa ń lo ewé yìí fún ìwòsàn àìsàn ibà, Ààrẹ inú, inú rírun, Jédíá-jé, ìgbẹ́ gbuuru, inú kíkún àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Ìwúlò rẹ̀ mìírànní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, wọ́n sábà máa ń jẹ́ egbò tàbí ẹ̀ka igi yí láti fi ṣe inọ̀-tótó èyí, àti láti fi pa àwọn kòkòrò búburú tí ó bá ń ṣàkóbá fún wa lẹ́nu..
wikipedia
yo