cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
O tun jẹ awọn oye ibile bi i séríkí ti ile Egba ati Baba Adini ti Musulumi Egba.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kẹsàn oṣù kẹta ọdún 2011, Ààrẹ Goodluck Jonathan yàn án gẹ́gẹ́ bí alága ìgbìmọ̀ lórí Àkọsílẹ̀ ìmọ̀ lórí ààbò àti ojúṣe abẹ́lé (Chairman, Presidential Committee on Public Awareness on Security and Civic Responsibilities) . Lateef Adegbitẹ jẹ́ arákùnrin sí olóògbé olókìkí àti ògbóǹtarìgì akọìtàn Ọ̀jọ̀gbọ́n Sabu BíòWA (1918-2001), ẹni tí ó ti jẹ́ Gíwá Yunifásítì ti Èkó tẹ́lẹ̀.Olórí Mùsùlùmí ní ijó Constituent ní ọdún1976, Adegbitẹ jiyan nípasẹ̀ nípasẹ̀ pé kí wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ ilé ẹjọ́ àpètún ti Islam sí àwọn Ìpínlẹ̀ tí ó wà ní gúùsù ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O sọ wipe awon Musulumi ni eto lati pe ki a se idajo won ni ibamu si ofin Sharia.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe é ́ ní àlàyé pé “àwọn Musulumi kò ní òfin àti ìlànà òmíràn yàtọ̀ sí èyí tí Sharia ti gbé kalẹ̀.. | wikipedia | yo |
Sharia gẹ́gẹ́ bí òfin mí yọrí jù gbogbo òfin ìlú àti ti ìhùwàsí lọ."Adegbitẹ fẹ́ ṣe níbó_*fún akitiyan M.K.O.. ) | wikipedia | yo |
Abiola lati ṣe agbekalẹ Sharia si awọn ipinlẹ guusu ni ibẹrẹ awọn ọdun 1990.. | wikipedia | yo |
O tun fi ipo yii mulẹ ni Oṣu kejila ọdun 2002 ni akoko ariyanjiyan ti o gbooro ni aarin awọn Kristiani ati awọn Musulumi.. | wikipedia | yo |
Adegbitẹ jẹ́ alága ìgbìmọ̀ àwọn arìnrìn àjọ mímọ́ ní Ìpínlẹ̀ Ògùn àti ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ àwọn Arìnrìn Àjò ti Orílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Nígbàtí Ibrahim Dasuki di Sultan ti Sokoto ní ọdún 1988 àti Ààrẹ-Gbogboogbo fún ìgbìmọ̀ gíga ti Nàìjíríà fún ọ̀rọ̀ Islam ní Nàìjíríà (NIAIA), AdélóAdegbitẹ ni wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bi Akọ̀wé-Gbogboogbo fún ìgbìmọ̀ náà.. | wikipedia | yo |
Lábẹ́ àkóso Adegbitẹ àti Dasuki ni nsIA, èyí tí wọ́n fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ ní ọdún 1974, di èyí tí ó tún bó ń ṣe iṣẹ́ pẹ̀lú ìtara.. | wikipedia | yo |
ní ìparí ọdún 2002 àti ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2003, Adegbitẹ ṣe àríyànjiyàn ti gbogbo ènìyàn pẹ̀lú òǹkọ̀wé gba ẹbun Nobel, Wole S̩ọ, ẹni tí ó fi ẹ̀sùn kan àwọn olùdarí musulumi pe wọ́n ru ìwà-ipá sókè lẹ́hìn rúdurùdu tí ó ṣẹlẹ̀ ní ìlú Kàdúná tí ó mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀mí ṣò.. | wikipedia | yo |
Ìbẹ̀rẹ̀ ọ̀tẹ̀ yí ní ìtako tí ó wáyé láti ọ̀dọ̀ àwọn Musulumi pé kí wọ́n ṣe nírí ìdíje arẹwà ọ̀dọ́bìnrin àgbáyé (Miss World) ní Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Origbòdìyàn yi tun bo gbérù si nitori o un ti àwọn Musulumi ka si gẹ́gẹ́ bi gbólóhùn òdì ni iroyin ti oniroyin, Isioma Daniel kọ sínú ìwé ìròyìn ti Kristiani kan pe ti o ba jẹ wipe Wowo ba lọ si ibi iṣẹlẹ arẹwà ọdọbìnrin agbaye yi ni, ko ba ti mu ọkan ninu àwọn oludije yi fi ṣe ìyàwó.. | wikipedia | yo |
Lẹhinna ni wọn sọ wipe igbakeji gomina ti Ipinle Zamfara, Mama Aliyu Shinka sọ oro gbangba pe o le je ofin fun Musulumi lati ta ẹjẹ Isioma Daniel sile.. | wikipedia | yo |
O ni níwọ̀n ìgbàtí akọiroyin yi kìí ṣe Musulumi ati wipe iwe iroyin yi ti toro gafara ni gbangba.Adegbitẹ sọ ninu iwe iroyin ti osu kewa odun 2003 pe ti won ba le yi ile Amerika ati awon alajọṣepọ rẹ lokan pada lati gba pe gbogbo ìpayà ti o nmule kàkiri agbaye yi o dinku ti idajo ododo ba le fi ese mule ni aarin ila-oorun.. | wikipedia | yo |
Ẹ fún àwọn ará Palestini ní ilẹ̀ wọn padà, ko si ní sí àyè fún Od Bin Ladens tí ayé yi láti gbérí.. | wikipedia | yo |
Nígbàtí UNESCO ṣe ètò àpérò lórí ọ̀rọ̀ àwọn ẹ̀sìn ní Abuja ní Oṣù kejìlá ọdún 2003, wọ́n pe AdélóAdegbitẹ láti sọ̀rọ̀ lórí ipa tí àwọn olùdarí ẹ̀sìn ńpọ̀ láti dẹ́kun rògbòdìyàn.IKÚ rẹ̀ Dókítà Adegbitẹ kú sí ìlú Èkó ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n, Oṣù Àsàn ọdún 2012.àwọn Ìtọ́kasíàwọn àwọn olókè ìire Ọjọ́ìbí ní 1933àwọn Ọjọ́lọ́ṣè ní 2012.. | wikipedia | yo |
Roger Scruton je is a Englimòye to gbajumo pataki fun ipa re si ìmòye aesthetics sugbon to tun gbajumo fun ise re lori oloselu.. | wikipedia | yo |
Ohun ni ẹlẹ́gbẹ́ iwadi àgbà ni gbangan àwọn ẹ̀kọ́ Kant àti Wittgenstein.Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1944.. | wikipedia | yo |
Olúrémi Comfort Sóná, a bí ní ọjọ́ kejì, oṣù Kẹ́ta, odún 1955, ó jẹ́ olóṣèlú kan gbòógì ní orílẹ̀-èdè Nàíjírìa, ọ̀mọ̀wé àti ònkọ̀wé ní.. | wikipedia | yo |
Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó díje fún igbákejì olòrí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní abẹ́ àsìá ẹgbẹ́ KÓWÀ ní ọdún 2015.. | wikipedia | yo |
ó fìdí rẹmi ní ọdún 2019 tí ó tún jáde gẹ́gẹ́ bíi aṣojú ẹgbẹ́ náà tí Dókítà Adésínà Fágbégbé Byron sì gbégbá orókè.Ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ Sónáná jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ìlú Ìbàdàn, Olú-Ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ alàkọ́bẹ̀rẹ̀ alapejuwe sẹnti lùkes, mọ́lẹ̀té, Ìbàdàn àti ilé ẹ̀kọ́ girama sẹnti ánnes, mọ́lẹ̀té Bakaana ní ìlú Ìbàdàn.. | wikipedia | yo |
O tẹsiwaju ninu ẹkọ rẹ lọ si Ile Eko giga ni Ile Ife (ti a npè ni Obafemi Awolowo Ilup bayii) nibi ti o ti kẹkọọ ede Faranse, o pari ni ọdun 1977.. | wikipedia | yo |
Ó gba Másításí ti Art nínu Lítíréṣọ̀ Faransé ní Unifásíà Cornell ní Amẹ́ríkà àti Mámasi ní Lìyáàkì ní ní Unifásírìa ní ọdún 1984.. | wikipedia | yo |
Ó padà sí Cornell ní ọdún 1988 láti lépa ètò ẹ̀kọ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú lingTIkì.ètò iṣẹ́ ní ọdún 1982, wọ́n gbaa ṣíṣe ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Obafemi Awolowo GẸ́GẸ́ bíi Igbakeji Igba OLÙKỌ́ ní abala àwọn tí ó n moju tó ètò ẹ̀kọ́ ède àjèjì, ó padà di ọ̀jọ̀gbọ́n nínú èdè Faransé àti lingTIkì ní ọdún 2004.. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Alexander von Humboldt Foundation, níbití wọ́n ti sọ ọ́ di Ambassador àwọn onímọ̀ sáyẹ́nsì láti 2008 sí 2014.. | wikipedia | yo |
ní ọdún 2010, ó fàgbà tì kúrò lẹ́nu iṣẹ́ ní Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ Unifásífí, ó dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú KÓWÀ , wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bíi alukoro ẹgbẹ́ ẹgbẹ́, wọ́n sì tún fàá kalẹ̀ ní ọdún 2015 gẹ́gẹ́ bíi olùdíje fún igbákejì igbákejì olórí orílẹ̀ orílẹ̀ lábẹ́ ẹgbẹ́ náà.. | wikipedia | yo |
Sónáìyà ṣe ipò kejìlá níbi ìtara pè|lú ìbò mẹ́rin dín lọgọrin lé lé gbẹ̀rún mẹ́tàlá.Àwọn àtẹ̀jáde Sónáìyà ní abala tí ó ń ṣiṣẹ́ lé lórí nínú ìwé ìròyìn ayélú já Nàìjíríà, Sónáìyà ti ṣe atejade ọdún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé pẹ̀lú pẹ̀lú | wikipedia | yo |
Àjọ Yorùbá Academy ní àjọ tí ó kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpele ẹ̀kọ́ àti àkójọpọ̀ àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ òṣèlú, okòwò àti àwọn onímọ̀ akọ́mọ́mọsẹ́ nípa èdè Yorùbá, àṣà ètò ọrọ̀-ajé, òfin, sáyẹ́nsì àti ìmọ̀ tẹkinọ́lọ́jì, àti ìmọ̀ ètò ìṣèjọba.. | wikipedia | yo |
Wọ́n dá àjọ yí sílẹ̀ ní ìlú Ìbàdàn, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní oṣù kẹwàá ọdún 2007, lẹ́yìn tí àwọn ọ̀dọ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nínú àwọn ìmọ̀ tí a ti mẹ́nu bá pinu lati padà sórílẹ̀-èdè bàbá wọn, tí ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re rene Group ń ṣàkóso rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ohun tí ó jẹ́ ìlépa wọn ni láti dá àbò àti láti tọ́jú èdè Yorùbá pàá pàá jùlọ àṣà àwùjọ àti ìdàgbàsókè àwọn ọmọ Yorùbá nílé àti lókè òkun.. | wikipedia | yo |
Nínú ìlépa wọn ni ki wón ma ṣe àkóso ìwé atúmọ̀ èdè Yorùbá láti lè fi ẹsẹ̀ èdè Yorùbá múlẹ̀ láàrín èdè tó kú lágbàáyé.. | wikipedia | yo |
Makòtò hasebẹ̀ (18/1/84) jẹ́ àgbà Boo Ori ọdán , Ọmọ Ọ̀rẹ́-Èdè Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1984àwọn ará Japanàwọn agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Japan.. | wikipedia | yo |
Festus Keyamo (ti a bi ni ojo kokanlelogun osu kini odun 1970) je agbejoro ati alagbawi agba (san) omo ile Naijiria, alatako, ati alamúsẹ́ eto eda eniyan.. | wikipedia | yo |
Ní oṣù keje ọdún 2017, Ìgbìmọ̀ tí ó ní ànfààní sí iṣẹ́ òfin ti ilẹ̀ Nàìjíríà, (Legal Vlée Privilege Committee) dárúkọ Keyamo gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn agbẹjọ́rò omo ilẹ̀ Nàìjíríà ti ó dayato láti fún ní ipò sàn.. | wikipedia | yo |
Keyamo ati awon miiran ti won daruko ninu akojopo oruko fun ipo san ni odun 2017 ni won se ifilole won sinu Ajumọṣe giga ti awon Alagbawi Agba Naijiria (SAN) ni osu kesan odun 2017 ni odun 2017 bakanna, Igbimọ Alakoso Àgbáyé ti America ti o wa ni Washington tun fun Keyamo ni ami eye eto eda eniyan ti agbaye fun awon akitiyan re lati opo odun seyin lori ti idaabobo ati igbega ti eto eda eniyan ati ipolongo fun ijoba Naijiria ti yio se isiro ise re.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kẹrin ọdún 2018, wọ́n yan Keyamo gege bi oludari fun ibaraenisoro (agbenuso osise) fun atunyan sipo ibo odun 2019 ti aare orile ede Naijiria.Igba ewe a bi Festus kayamo ni ojo kokanlelogun osu kini odun 1970 ni Ughelli, ilu kan ni ipinle Delta ni guusu Naijiria sugbon baba re wa lati EFfurun, ilu kan ni ipinle Delta bakanna.. | wikipedia | yo |
Keyamo ko eko onípele kini re ni ile-iwe alakobere ti Model ati eko onípele keji ni ile-iwe giga ti ijoba ti o wa ni ughhe nibiti o ti gba iwe eri oniwe mewa (West African School Certificate) ni odun 1986.. | wikipedia | yo |
Lehinna, O lọ sí Yunifásítì Ambrose Alli tí ó wà ní Ẹkwupoma ní Ìpínlẹ̀ Edo, gúúsù Nàìjíríà níbití ó ti gba oyè àkọ́kọ́ nínu ìmọ̀ òfin ní ọdún 1992.. | wikipedia | yo |
O si gba ipe si pepe amofin ti orile ede Naijiria ni osu kejila odun 1993.Iṣẹ ofin Festus Keyamo bere ise ofin re ni odun 1993 ni ile ise ofin ti Gani Fawehinmi ti o wa ni Ipinle Eko, guusu Naijiria.. | wikipedia | yo |
Lehin ti o lo odun meji ni ile ise ofin ti Gani Fawehinmi, o kuro nibe lati lo se idasile ile ise ofin Festus kayamo.Keyamo je agbejoro fun Mujahid Dokubo-asa, eni ti o je olori fun Niger-Delta Peoples Volunrance Force, nigbati won pee lejo fun Onidida ilu.. | wikipedia | yo |
O un tun ni olori agbejoro fun Ralph Uroshuruuruke, olori fun egbe ajàble lati je ki idaduro ipinlẹ Biafra wásí imuse (!B), nigba ìpéjọ rẹ fun didalẹ ilu.. | wikipedia | yo |
Keyamo tun je okan lara awon agbejoro fun iku Bola Ige.Ni odun 2008, o gbe ijoba apapo ile Naijiria lo si ile-ejo lori yiyan awon olori ise lona to lodi si ofin.Ni odun 2017, arabinrin Stephanie Ooto, akorin kan ti o fi ilu Canada se orisun, fi esun kan Aposteli Suleman Johnson latipase Festus Keyamo, eniti nse agbejoro re, pe Aposteli Suleman kúnná lati mu ileri igbeyawo ti o se pelu oun se lehin igba ti o ti ba oun ni ibalopọ lopolopo igba.. | wikipedia | yo |
Keyamo tun je agbejoro fun awon olokiki olorin omo ile Naijiria ti won npe ni Duo of £square ati laarin ariyanjiyan fidio ti o nlo látinú eyi ti o se afihan awon arakunrin mejeeji yi nibiti won ti nbu ara won ti won tun nkan ara won ni ese.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn èyí ni Festus Keyamo se agbejade ilodi si fidio yi tí ó sì see lalaye pé fidio yí ko ti Ile-iṣẹ Òfin oun jade.yiyan sinu oselu Festus wa lara awon Minisita ti a yan fun isakoso ijoba eleekeji ti Aare Muhammadu Buhari.. | wikipedia | yo |
lẹ́hìn tí wọ́n ti yàn, ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ṣe àyẹ̀wò rẹ.. | wikipedia | yo |
Titi di ojo kẹrinlelogun osu kesan odun 2019, won yan Keyamo gege bi Minisita Ipinle fun Niger Delta, ki o to di wipe Aare Muhammadu Buhari yan pada si ile ise ijoba ti o garner oro osise ati ìgbanisíṣẹ́, laarin osu kan si igba ti won ti koko yan ni ojo kokanlelogun osu kejo odun 2019.. | wikipedia | yo |
àwọn ìtọ́kasí àwọn ẹ̀nìyàn aláàyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1970.. | wikipedia | yo |
Sunday Dare ni a bi ni ojo kokandinlogbon, osu karùún odun 1966 (29-5-1966) je ògbónta oníwèé-iroyin omo ile Naijiria ti o ti sise ni opolopo ile-ise iwe-iroyin ti sise ni oniruuru ile-ise igbohun safefe redio ati ile-ise atewe-iroyin, o sin ni imo to funra fun odidi odun mẹẹdọgbọn gbáko ninu ise yii mi-agbako ti Nigerian Communications Commission (NCC), Aare ( President of the Federal Republic of Nigeria Muhammadu Buhari ni o yan-an si ipo naa ni osu ìkẹjọ odun 2016.lowolowo bayii, o je Minisita fun eto nipa ọdọ ati ere-idaraya ti orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ Buhari yán-án sí ipò Mínísítà ní ọjọ́ kọkànlégún, oṣù Kẹẹ̀jọ, ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Oba (Aholu, ti o tumọ si ọba lede Ogu) Akran ti ilu Badagry je oruko oye oba ni ilu Badagry.. | wikipedia | yo |
Oruko oba Akran ti Badagry ti o wa lori oye lowolowo ni De WWno Aholu Babatunde Garyi i.. | wikipedia | yo |
Àkànlò -èdè ni ìpèdè tàbí lílo ọ̀rọ̀ ní ọ̀nà tí ìtumọ̀ rẹ̀ yàtọ̀ gédégbé sí ìtumọ̀ ọ̀fẹ́o tàbí ìtumọ̀ ṣákálá.. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ lílò ọ̀rọ̀ tàbí awẹ́-gbólóhùn lọ́nà tó jinlẹ̀ tí ìtumọ̀ rẹ̀ yàtọ̀ sí ìtumọ̀ ọ̀rẹ́fẹ́.. | wikipedia | yo |
Oun ni ìpèdè tí gbolohun inú rẹ̀ kò ní nǹkankan ṣe pẹlu ìtumọ̀ rẹ̀.Awn tọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ìlú Èdè jẹ́ ìlú kan tí ó gbajúmọ̀ níṣe Yorùbá ní ìpínlẹ̀ Osun lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
tìmí ti ìlú èdè ni orúkọ oyè ti ọba aládé ti ó n pàṣẹ ilú náà n jẹàwọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Olùwo ti Ìlú Ìwọ ni orúkọ oyè Ọba Aládé tí ó ń jọba ní ìlú Ìwó.. | wikipedia | yo |
Iwo jẹ ilu kan ti o gbajumọ nílé Yoruba ni Ipinle Osun ni orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Oba Abdul-rahheed Akanbi Adewale ni oba ti o wa lórí oyè lọ́wọ́lọ́wọ́ ní Ìlú Ìwó.. | wikipedia | yo |
Ìlú Ẹ̀pẹ́ jẹ́ ìlú kan gbòógì tí o gbajúmọ̀ n'ilẹ̀ Yorùbá ní ìpínlẹ Èkó lápá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Ẹ̀pẹ́ jẹ́.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ olú-ìlú ìjọba ìbílẹ̀ èpè (Èpè local government)... | wikipedia | yo |
Iṣẹ agbe ati ẹja pipa ni iṣẹ ibile wọn n'ilu Epe.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Frank James Lampard jẹ agba-oje agbabọọlu-afẹsẹgba ti orilẹ-ede United Kingdom.. | wikipedia | yo |
Ọtí fìgbà kan jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ikọ̀ Chelsea kí wọ́n tó wá yàn-án láìpẹ́ yìí gẹ́gẹ́ bí akọnimọ́-ọngba fún ikọ̀ Chelsea bákan náà lọ́dún2019.. | wikipedia | yo |
Gẹgẹ bi agbabọọlu, o jẹ ogbontarigi agbabọọlu aringbungbun ori papa lasiko rẹ̀.. | wikipedia | yo |
A bí Frank Lampard ní ogúnjọ́ Oṣù Kẹfà Ọdún 1978.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Awon obinrin alain pupa {wi} , je agbekale ise lati di ejo laarin okunrin si obinrin lori ero ayelujara ti Wikipedia.. | wikipedia | yo |
Àwọn obìnrin alámí pupa jẹ́ àkànṣe iṣẹ́ WikiProject lórí ẹ̀rọ Lorijà yanjú ìdojúkọ láti ṣẹ̀dá àwọn nkan nípa àwọn obìnrin olókìkí tí kò sí níbẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí... | wikipedia | yo |
ìfiyèsí láti mọ̀ nípa àwọn àkọ́lé tí ó sọnù ní láti wo àwọn Hyperlink pupa nínú àwọn tí wọ́n ti ṣẹ̀dá wọn tẹ́lẹ̀ìtàn-àkọ́ọ́lẹ̀ Wikipedia.. | wikipedia | yo |
Ìrètí Opesemi jẹ́ ogbontarigi òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó sì maá n ṣe fíìmù ní èdè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì.ibẹrẹṣe ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ ọjọ́ kẹrìnlá, oṣù kìíní, ọdún 1982 ni a bí ójì sí apá gúùsù ti apá ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ìpínlẹ̀ Èkó, ní Lagos State Primary School ni ó ti bẹ̀rẹ̀ ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ tí ó sì parí.. | wikipedia | yo |
O gboye ninu ẹkọ Economics ni Lagos State University.. | wikipedia | yo |
Ó ti ṣiṣẹ́ lóri ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré bíi; heavy Storm, ìfẹ́ owó, Spiritual War, tówó tọmọ, Oreke Gpe àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ tó ti gbaawọn itota.. | wikipedia | yo |
Taiwo Hassan ti inagijẹ re n je ògo ni a bi ni ojo kokanlelogbon osu kewaa odun 1959 (31-10-1959).. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ agbá òsèré, olóòtú, olùdarí eré orí ìtàgé àti sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú Ìlaròó ní Ìpínlẹ̀ Ògùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìtọ́kasí àpón lórí Interyàrá àwọn Ọjọ́ìbí ní 1959.. | wikipedia | yo |
Ayọ̀ Adesanya (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù Kẹjọ ọdún 1969) jẹ́ agbá òṣèrébìnrin, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì.. | wikipedia | yo |
Ayọ̀ Adesanya máa ń ṣàfihàn nínúu eré Yorùbá àti ti Gẹ̀ẹ́sì.ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé rẹ Ogùngu, ní ìlú Ìjẹ̀bú, ní ìpínlẹ̀ Ògùn ní Ayọ̀ Adesanya ti wá, ìyẹn ni apá gúúsù ti apá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Anne's ní ìlú Ìbàdàn ni ó ti kàwé, fún ti alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ti girama.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn náà, ó lo University of Ìbàdàn láti lọ kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú Mass Communication.Iṣẹ́ rẹ̀ Ayọ̀ Adesanya bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 1986 lẹ́yìn tí ó sin orílẹ̀-èdè rẹ̀ tán, ìyẹn NYSC.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1996, ó darapọ̀ mọ́ àwọn tí ń ṣe eré àgbéléwò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Fíìmù Tunji bamishi tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Palace ni wọ́n ti kọ́kọ́ ṣe àfihàn rẹ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́.. | wikipedia | yo |
O pada darapọ mọ́ ẹgbẹ́ awọn ti n ṣe fiimu Yoruba.. | wikipedia | yo |
Nígbà náà ni ó bẹ̀rẹ̀ sí ní darí ère, tó sì ń gbé ère jáde.. | wikipedia | yo |
O ti gbe ọpọlọpọ ere jade, o si ti dari ere pupọ.. | wikipedia | yo |
Ayọ̀ Adesanya tún máa ń ṣe fíìmù Yorùbá àti ti Gẹ̀ẹ́sì.Ayé rẹ̀ Ayọ̀ Adesanya fìgbà kan jẹ́ ìyàwó goríi Hassan, àmọ́ wọn ò fẹ́ ara wọn mọ́ báyìí.. | wikipedia | yo |
Ó bí ọmọkùnrin kan.díẹ̀ lára àwọn fíìmù rẹ̀ remember Your Mother (2000) dancer 2 ( 2001) Tears in my heart 2 (2006)àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Lára èso yìí ni a ti máa ń ṣe epo pupa àti epo Adi-ṣoṣo.. | wikipedia | yo |
Awo pípọ́n ara eso yii ti a mọ si ẹyin-èkùrọ́ ni a ti n ro epo pupa, èkùrọ́ inu rẹ ni a ti a ro epo adi-soso.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
adelé (régént) ní ilẹ̀ Anti-o-jiji (Yorùbá) ni èni tí a yàn láti darí ìlú tí ọba wọn bá wàjà tí àṣà wọn kòsì fàyè gbà á pé kí orí ìtẹ́ ọba náà ṣòfò.. | wikipedia | yo |
adelé a máa darí ìlú tí ọba wọn bá ń ṣàárẹ̀ tàbí tí kò lè dáńtọ́ mọ́ láàárín ìlú.. | wikipedia | yo |
Ó máa ń ní ìwọ̀nba ìgbà tí adelé máa fi ń wà lórí ìtẹ́.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Dr Oluranti Adebu, (ti a bi ni ojo ketadinlogbon osu Kọkànlá odun 1970) je oloselubinrin omo Yoruba lati ipinle Eko lorilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ ọmọ bíbí ìdílé Ìdòwú-ES ti ikú òjò Òjòrọ ní ìjọba ìbílẹ̀ ọjọ́, ni ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Oun ni Igbakeji Gomina ipinle Eko nigba ijoba gomina Akinwunmi Ambode ti saa won sese pari ni odun 2019.. | wikipedia | yo |
Obafemi Hamzat ni o rọpo re gegebi Igbakeji Gomina.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Olusoagutan Enoch Adejàre Adeboye (ni a bi ni ojo keji osu keta odun 1942) je ojise Ọlọrun ati Oluṣọwe Àgùntàn-Àgbáyé ti Ijo Oniràpada ti a mo si the Redee Christians Church of God (CRC–G).. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ ọmọ bíbí Ifẹ̀wàrà, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga University of Nigeria (UNN) ní Nsukka ṣùgbọ́n nítorí ogun abẹ́lé Nàìjíríà, ó parí ìwé-ẹ̀kọ́ àkọ́kọ́ rẹ ní University of Lagos tí o gba oye oye oye ni ìmọ̀-ìwé gíga ní ìmọ̀-ẹ̀kọ́ ní ọdún 1967.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1969, ó gba oyè ní hydroDynamics láti University of Lagos.. | wikipedia | yo |