cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
O darapọ mọ ile ijosin Kristiẹni rẹmedmed ti Ọlọrun ni ọdun 1973..
wikipedia
yo
O ṣe itumọ ede Yoruba si Gẹẹsi fun Olusoagutan Josiah Olufemi AkinDayomi.pe si Iṣẹ-iranṣẹo jẹ alufaa ti ile ijosin ti rẹmedmed Christian Church ni ọdun 1977o di olutọju gbogbogbo ti ile ijosin ni ọdun 1981.Ile ijosin naa, eyiti a ko mọ daradara ṣaaju Adeboye di olutọju gbogbogbo, lọwọlọwọ ni ọpọlọpọ awọn ẹka ni kariaye ni awọn orilẹ-ede 196..
wikipedia
yo
Adeboye ti ṣàlàyé pé èjú rẹ̀ ní láti fi ilé-ijọsin wà láàrin Ealní ìkajú márùn ìkájú íjọ ní àwọn ìlú Ìdàgbà àti ìṣẹ́jú awakọ̀ márùn ní àwọn ìlú tí ó Odàgbàsókè. àwọn ẹ̀bùn àti Ìgb'ikán nínú àwọn Àásì Àáta jùlọ ní àgbáyé' (2008'' (2008) ìka sí ìkàn..
wikipedia
yo
Oyedépò (ti a bi ni ọjọ keta-din-lọgbọn osu Kẹsán ọdun 1954) jẹ ọmọ orilẹ-ede Naijiria, ojise Ọlọrun Bíṣọ́ọ̀bù-Àgbà, ati oludasile ijo Living Faith Church Worldwide (ijo igbàgbọ́ aaye to Kariaye) ti gbogbo ẹ̀nìyàn mọ si Winners' Chapel (Ìjọ aṣẹ́gun)..
wikipedia
yo
Olú-Ìjọ yìí fún gbogbo àgbáyé ni a tẹ̀dó sí ìlú Ọ̀tá ní ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà Oyèdépò ni oníwàásù ọlọ́lá jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú iye àpapọ̀ tí ó ju us $ 150 mílíọ̀nù dọ́là.Ìgbésí ayé àti ìtàn ní ọjọ́ kẹtà-lé-lọ́gbọ̀n oṣù kẹsàn ọdún 1954 ni wọ́n bí David nìyíníyì Oyèdépò ní ìlú Òṣogbo, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ṣugbọn ó jẹ́ ọmọ bíbí ìlú ọmú-Aran, ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ìrẹ́pọ̀dùn..
wikipedia
yo
Ibrahim baba rẹ̀ jẹ́ olùtọ́jú Mùsùlùmí.Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìjọ Kérúbù àti Serafu.nígbàtí ó dàgbà ní ìyá-nlá rẹ̀ ní Òṣogbo, ẹnití ó ṣàfihàn rẹ̀ sí àwọn iṣẹ́ ti ìgbésí-ayé onígbàgbọ́ nípasẹ̀ àwọn àdúrà òwúrọ̀ tí ó lọ pẹ̀lú..
wikipedia
yo
O tun kọ ọ ni pataki idamẹwa.oye di "Aobitò" ni ọdun 1969, nipasẹ ipa ti olukọ rẹ, Betti LASHer, eniti o nifẹ si re ni awọn ọjọ ile-iwe giga ..
wikipedia
yo
Ó kọ́ ẹ̀kọ́ fàájì ní ilé-iṣẹ́ Polytechnic Ìlọrin ti Kwara àti pé ó ṣiṣẹ́ ní ṣókí pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Federal ti ilé ní Ìlọrin Owa fi iṣẹ́ rẹ̀ lé láti dojúkọ iṣẹ́ ìhìnrere..
wikipedia
yo
rẹ̀gẹ́gẹ́bí rẹ̀, ó gba àṣẹ kan láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run nípasẹ̀ ojúran méjìdínlógún – Ní oṣù karun, ọdún 1981, láti gba òmìnira kúrò nínú gbogbo ìrẹ́jẹ ti èṣù nípasẹ̀ ìwãsù ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́.Ilé Ìjọsìnoyetérà, ní ọdún 1998 ni Ọlọ́run pàṣẹ pé kí ó kọ́ ilé ìjọsìn titun fún ìgbìmọ̀ náà láti gba nọ́ḿbà tí ó pọ̀ sí ti àwọn olùjọsìn..
wikipedia
yo
'agùtan igbagbọ', eyiti a sọ pe o jẹ ile ijosin ti o tobi julọ ni agbaye..Ìwàásù Kristiẹni== Awọn ẹkọ rẹ ti gbe e si kilasi ọrọ igbagbọ awọn oníwàásù bii Kenneth copeland awọn..
wikipedia
yo
Abáwọn (Stid) jẹ́ eré oníṣe láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a gbé jáde ní ọdún 2013..
wikipedia
yo
Eré oníṣe yìí dá lórí ReDI sí tí àwọn ènìyàn tí àrùn kóKògbóògùn, áá ń bá fínra ń dojú kọ..
wikipedia
yo
Diminas Dagogo ni olùdarí eré náà nígbàtí àwọn gbajúgbajà òṣèré bíi Jackie Appiah, Hilda Dokubo àti Emeka Ike kópa nínú eré náà..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ elétò Ilera ti Ìpínlẹ̀ Rivers ni o se agbejade ere naa.Ètè/agbekalẹ ere..
wikipedia
yo
Ọ̀gá tí a tún lè pè ní Agẹmọ jẹ́ ẹranko kan tó farajọ aláǹgbá, ṣùgbọ́n tí ó ní àbùdá kan tí ó lè fi pàrọ̀ àwọ̀ èyíkéyí tí ó bá fẹ́..
wikipedia
yo
Ọ̀gá lè lọ tó ọdún mẹ́ta sí Márù-ún kí o tó kú.Àwọn ìtọ́kasíàwọn aláǹgbá..
wikipedia
yo
Ọmọlúàbí jẹ́ gbólóhùn tí ó fi ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àṣà àti ìṣe àwọn baba ńlá bàbá Yorùbá hàn nípa ọgbọ́n inú àti inọ̀ ikùn láti fi ṣàpèjúwe ìwà rere tí ó tọ́ kí ènìyàn ó ma hù láwùjọ..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀, gbólóhùn yĩ fi ìwà Akin, ìjàramọ́ṣẹ́ , ìwà ìrẹ̀ ìrẹ̀lẹ̀ àti àpọ́nlé, tí ń bẹ lára àwọn Yorùbá..
wikipedia
yo
Ẹni tí a è pè lọ́mọlúàbí ni ẹni iyì, tí ó gbàgbọ́ nípa ìjáfáfá lẹ́nu iṣẹ́ ẹni, tí ó ń bọ̀wọ̀ bọ̀wọ̀ fún ẹ̀tọ́ ọmọlàkejì rẹ̀, tí ó sì ń ṣojúṣe rẹ̀ láwùjọ níbi ìfarajìn àti ìnọwọ́sí..
wikipedia
yo
Sàkáyanrí, ìwà ni ó jẹ́ ọmọ tí Olú (Olódùmarè) bí ..
wikipedia
yo
Ẹni tí ó bá jẹ́ ọmọlúàbí yóò hùwà tí ó dára jùlọ tí ẹlòmíràn lè kọsẹ̀ nínú ìwà pẹ̀lẹ́..
wikipedia
yo
ÌWÀ pẹ̀lẹ́ ni gbòngbò tí a fi ṣẹ̀dá àṣà àti ìṣe Yorùbá , tí o sì ń orígun kan nínú ìwà ọmọlúàbí..
wikipedia
yo
ìtẹríba(respect) inú rere (Good Will, having a good mind towards others) òtítọ́ inú (Truth) ìwà rere (Good character) Akiakànńju (Brap) títẹ mọ́ iṣẹ́ (Hardwork) ọpọlọ pipe (Intelligence)Ó seni tí a kò le pe lọ́mọlúàbí láì kò fi ti ẹ̀sìn kan ṣe..
wikipedia
yo
Èyí túmọ̀ sí wípé ìwà ọmọlúàbí jẹ́ ohun pàtàkì tí àwọn ẹlẹ́sìn mú ní ọ̀kúnkúndùn tí wọ́n sì ń kọ́ àwọn olùkópa nínú ẹ̀sìn wọn, nípa kí jíjẹ́ olòjo, oníwà ìrẹ̀lẹ̀, kí a sì ma sòtítọ́ nígbà gbogbo ẹ̀sìn wọn yálà nínú ẹ̀sìn Kristẹni tàbí ẹ̀sin and Mùsùlùmí.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Omoyele Sowore (tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndíndínlógún osù kejì ọdún 1971, 16-02-1971) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn..
wikipedia
yo
ó díje dupò ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lábẹ́ ẹgbẹ́ olóṣèlú “African Action Congress" lọ́dún 2019, òun náà ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn elérò àtàgbà, Sahara Reporters..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kẹjọ ọdún 2019, àwọn Ọlọ́pàá Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ fi ṣìnkún òfin mú Sowore nítorí ó ṣe agbátẹrù ìfẹ̀hónúhàn láti gba ìjọba lọ́nà àìtọ́.Àárọ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀yele Sowore jẹ́ ọmọ ẹsẹ̀-ọ̀dọ̀, ìpínlẹ̀ Òndó ní gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà, a bí ní agbègbè Niger Delta níbi tí ó ti dàgbà ní ilé olórogún pẹ̀lú ọmọ mẹrindilogun..
wikipedia
yo
nígbà tí ọpẹ́ ọmọ ọdún méjìlá, ó kọ́ bí a ṣe un wa ọ̀kadà kí ó lè má lọ sí odò ní àárọ̀ ojojúmọ́ láti pẹja fún gbogbo ẹbí rẹ̀ kí ó tó lọ sí ilé-ìwé..
wikipedia
yo
Sowore kẹ́kọ nípa "Geography and Planning” ní Yunifásítì ti ìlú Èkó láàrín ọdún 1989 sí 1995, OpariParish nónó pé Leọ̀làjúsíra) kúrò lára àwọn akọẹ̀kọ́ ilé-ìwé rẹ̀ ní méjìméjì nítorí ọ̀rọ̀ tí ọjọ́ mọ́ òṣèlú àti ìjà fún ẹ̀tọ́ ọmọ ilé-ìwé..
wikipedia
yo
ó jẹ́ ààrẹ ìjọba “Student Union Government” ti Yunifásítì ti ẹ̀kọ́ láàárín ọdún 1992 sí 1994..
wikipedia
yo
Sowore gba ami-eye master degree ni "Public Administration" ni Yunifasiti ti Columbia.Sahara ReportersSowore da Sahara Reporters kalẹ̀ ní ọdún 2006 ní ìlú New York láti láti gbógun ti ìwà ìbàjẹ́ àti ti ìjọba tí kò tó..
wikipedia
yo
Ile-iṣẹ Ford Foundation ati Omidyar Foundation ni òún ṣe atìlẹ̀yìn owó fún ilé iṣẹ́ Sahara Reporters ..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi ofin rẹ, Sahara ko un gba ipolowo tabi atilẹyin owo lati ọdọ ijọba Naijiria.idije fun ipo àárẹ̀ni ọjọ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣu keji ọdun 2018, Sowore kede ero rẹ lati dije fun aarẹ ninu idibo gbogbogbòò 2019 ti Naijiria Ni oṣu kejo ọdun 2018, o da ẹgbẹ oṣelu kan ti a n pe ni "African Action Congress" (AAB) kale..
wikipedia
yo
Ni ojo kefa osu kẹwàá odun 2018, a se idibo alabélé ti egbe oselu ACP, Omoyele Sowore si jade laisi atako gege bi oludije Aare fun ẹgbẹ naa bi o tile je wipe Ofidi remi ninu idibo gbogbogbo odun 2019, Sowore ni ibo 33,953, eyi ti ọmú ko je eni ẹkarun ti o ni ibo Topoju.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Jean Maurice Eugene Clement lẹ́kọ̀ọ́teau to gbájúmọ́ bí Jean lẹ́kọ̀ọ́teau (; 5 July 1889 – 11 October 1963) jẹ́ Olùkọ̀wé, Akéwì, àkún àwòrán, njagun oníṣẹ́ àti olùdarí fíú ara Fránsì.Àwọn Olùkọ̀wé Ara Fránsì..
wikipedia
yo
Ẹ̀yà Ogu (Ogu people) tí ọ̀pọ̀ eniyan máa ń sí pé ni ègún jẹ́ ẹ̀yà ti tẹ̀dó sí ìpínlẹ̀ Èkó ati ogun lápá gu-ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Àwọn ẹ̀yà Ogu ní oniruuru èdè-àdúgbò bíi’, thevi, WWFI, ṣètò, Toli, ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
Àwọn Òjí tó ìwọ̀n ìga mẹ́ẹ̀dógún (15%) ní àpapọ̀ àwọn olugbe Ìpínlẹ̀ Èkó Èkó..
wikipedia
yo
Orísun wọn Àwọn Ẹ̀yà Ógù ṣe wá láti orílẹ̀-èdè Àtijọ́ Dáhomeh tí a mọ̀ nísinsìnyí sí orílẹ̀-èdè òmìnira Benin (Benin Republic) ìtàn àtẹnudẹ́nu kan sọ wípé àwọn Ógù jẹ́ ìran kan tí wọ́n ṣẹ̀ wá láti WWFI, Àlátha àti Weme tí wọ́n jẹ́ ìlú tí ó wà lórílẹ̀-èdè Olómìnira Benin lẹ́yìn ogun Dahomey tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní Sétúrì méjìdínlógún sẹ́yìn (18th century)..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi Olùṣọ́tan Mesáwaku ṣe sọ ninu ìwé rẹ kan, awọn ẹya Ogu wá tẹ̀dó sí Badagry lati Ajetúrì mẹẹdogun (15th century) sẹ́yìn nitori aabo nigba ogun Dahomey..
wikipedia
yo
Reuben Fásanrántí jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tà!’rùún (93) láti ìpínlẹ̀ Òndó lápá gúsù ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ó ti fìgbà kan jẹ́ olórí abala kan nínú ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re, ẹgbẹ́ tí o ń ṣe kòkárí òṣèlú àti ìdàgbàsókè ilè Yorùbá lápapọ̀..
wikipedia
yo
Ó kọ̀wé fipò adarí afẹ́nifẹ́re sílẹ̀ lọ́dún 2015.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
mide Funmi Martins (ti a bi ni ojo kejila osu kerin odun 1979) je osere-binrin ati olootu sinima agbelewo omo Yoruba lorilẹ-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ gbajúgbajà òṣèré-bìnrin olóògbé fúnmi Martins tó ṣaláìsí lọ́dún 2002..
wikipedia
yo
mide Martins darapo mo awon osere sinima agbelewo ni keteti iya re di oloogbe..
wikipedia
yo
Ó fẹ́ òṣèré, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò tí a mọ̀ sí àfẹ́èṣì owó..
wikipedia
yo
Káyọ̀dé Akintemi tí wọ́n bí ní (June 26, 1965) jẹ́ Akọ̀ròyìn , TV presenter, Onímọ̀ ni ọ̀rọ̀ tonlo (subject Matter Exls), alámòójútó isẹ́ àkànṣe, Olú Funílà nípa ICT ICT ( ICT Bad) , Ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé iṣẹ́ iṣẹ́ Channels TV, gẹ́gẹ́ bí olóòtú àgbà àti gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà fún ẹ̀ka ICT ICT àti alámòójútó iṣẹ́ àkànṣe fún London gúnlé hilling 🙂don
wikipedia
yo
Ó fi ilé iṣẹ́ amóhùmáwòrán Channels sílẹ̀ ní ọdún 2016 láti lọ dá tirẹ̀ sílẹ̀ tí ó pè ní Plus TV Africa, níbi tí jẹ́ aláṣẹ àti olóòtú àgbà fún ìgbé ìròyìn jáde.Káyọ̀dé ló ma ń gbàlejò àwọn ènìyàn lórí ètò tí ó pè ní Sunrise Saturday, tí ó ma ń gbinàyá ní orí ìkànì Channels TV..
wikipedia
yo
Òun tún nósì ma ṣètò ṣètò “Wake Up Africa",èyí tí ó ma ń wáyé ní gbogbo ọjọ́ Ẹtì láàrín agogo mẹ́fà sí ago mẹ́sàán àárọ̀ (6 a.M and 9.am), lórí ìkànì Rédíò 94.3 FM.ètò ẹ̀kọ́ àti ìgbòkègbodò iṣẹ́ rẹ̀ Káyọ̀dé gba ìwé ẹ̀rí Higher National diploma nínú ìmọ̀ -EE Mass Communication amo tí ó yan Broadcast Journalism láàyò jùlọ ní ilé-ẹ̀kọ́ Gbogbonìṣe ti Ìpínlẹ̀ Ògùn tí nwọ́n ti yí padà sí Moshood Polytechnic báyí.Lẹ́yìn èyí ni ó gba ìwé-ẹ̀rí Postllow diploma nínú ìmọ̀ Information Technology.Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìgbóhùn sáfẹ́fẹ́ ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1980s pẹ̀lú ilé ìgbóhùn sáfẹ́fẹ́ ikẹ̀ Nàìjíríà (Radio Nigeria) gẹ́gẹ́ bí atọ́kùn fún ètòTeen and Twenty Beats.Nígbà tí ó di ọdún 1987, Ó dara pọ̀ mọ́ Ogun State Broadcasting Corporation, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ fún ọdún mẹ́ta ṣáájú kí ó tó di òṣìṣẹ́ fún ẹ̀ka-ìmọ̀ ẹ̀kọ́ Mass communication ní Fásitì Ahmadu Bello ní ọdún 1991..
wikipedia
yo
Ó dara pọ̀ mọ́ Ogun State Television gẹ́gẹ́ bí olórí fún ẹ̀ka ètò amóhùmárá ní ọdún 1993, Ó ṣẹ̀dá ẹ̀ka ( Independent production company), tí wọ́n pè ní “The Kay Associate" pẹ̀lú ọmọba Kẹ́hìndé Adeosun, tí ó jẹ́ alága tẹ́lẹ̀ fún (Promosemose advertisement).Ní ọdún 1994, ó gbéra lọ sí ìlú London, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ilé iṣẹ́ BEN Television, tí ó jẹ́ ilé iṣẹ́ ìgbóhùn sáfẹ́fẹ́ ti ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Ní oṣù kẹta ọdún 2011 ó dára pọ̀ mọ́ iké iṣẹ́ amóhùnmáwòrán Channels TV gẹ́gẹ́ bí Olóke àgbà fún àjọ náà títí di ọdún 2016.Ní ọdún 2013, wọ́n yan án àmì ẹ̀yẹ Nigerian Broadcasters Merit Awards gẹ́gẹ́ bí “Best Station's Manager of the Year", ọdún yìí kan náà ni wọ́n fún ilé iṣẹ́ Channels TV ní àmì ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí ilé iṣẹ́ amóhùnmáwòrán tí ó dára jùlọ ní ọdún náà.Ní January 2013, Kayode bu ẹnu àtẹ́ lu ìróyí ẹlẹ́jẹ̀ kan tí ó ń jà ràìn ràín wípé àpérò kan tí ilé iṣẹ́ Channels TV gbé kalẹ̀ lórí bí IGdàgbàsókè ṣe lè débá àwọn Agbófinró Nigerian Police Force ni Ìjọba Àpapọ̀ Federal Government of Nigeria.Ó sọ àsọ minu ọ̀rọ̀ lórí rẹ̀ wípé ìfòté lé àpéjọ Ìjíròrò náà ni ìjọba ri wípé àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ nípa ètò àbò ti kópa. Ẹgbẹ́ rẹ̀ Akintemi jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ti ọ̀jọ̀gbọ́n, ti Royal Television Society àti ti ti ilé- ẹ̀kọ́ rédíò ..
wikipedia
yo
O tun jẹ ọmọ ẹgbẹ ti awujọ ti o wa fun iṣakoso alaye ọest ..
wikipedia
yo
àti Ilé- Iṣẹ́ Àwọn Olùdarí .Ẹ tún lè wo John mọmọhitakùn ìjásóde MD/CEO Káyọ̀dé Akintemi ↑ About Plus TV AFRIOC Itaọkà si Àwọn Ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1965..
wikipedia
yo
Gabriel Akinọlá Dè tí wọ́n bí í ọjọ́ kaẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kẹwàá, ọdún 1913( 30-1-1913) tí ó sì kú ní ọjọ́ Kárùún oṣù Kọkànlá , ọdún 1987 ( 5 November 1987).Ni ó jẹ́ oní onídẹ́ iṣẹ́ ẹ̀kọ́lé àti Mínísítà fún ètò o aètò ọ̀gbìn nígbà kan rí apá ìwọ̀ Oòrùn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó tún jẹ́ ọ̀rẹ́ tímọ́ tímọ́ Olóyè Awólọ́wọ̀ Awówò..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí Mínísítà, ó kópa ribiribi nípa mímú ìlọsíwájú bá ètò ìgbniṣíṣẹ́ àwọ́n àsẹ̀sẹ̀ yọ ọ̀gọ́ tí wọ́n kàwé jáde ní fíkí tí wọ́n sì nífẹ̀ẹ́ sí iṣẹ́ àgbẹ̀ tí ìjọba yóò ma kọ́ wọn ní iṣẹ́ ọ̀gbìn ní àwọn ìletò tí wọ́n ti kọ́ kalẹ̀ fún iṣẹ́ àkànṣe náà tí ìjọba yóò sì ma fún wọn ní owó ọ̀yà..
wikipedia
yo
dídá àwọn ìletò wọ̀nyí ni wọ́n jẹ́ ètò àyálò láti ọ̀dọ̀ àwọn Isráẹ́lì ..
wikipedia
yo
ètò yí wà fún láti já ọkàn àwọn ọ̀dọ́-langba kúrò nínú èrò wíwáṣẹ́ lọ sí àwọn ìlú ńlá ńlá tí wọ́n sì yàn iṣẹ́ àgbẹ̀ ni posin.Akin dékó ní wọ́n bí ní ìlú Ìgbòtu, ní ìpínlẹ̀ Oǹdó, tí àwọn òbí rẹ̀ sí jẹ́ ọmọ ìlú Ìdanrẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Òndó kan náà..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ St Peters,ní Ìpínlẹ̀ Èkó, fún ètò ẹ̀kọ́ Alákúkúbẹ̀rẹ̀ àti ti ìpele ọlọ́dún mẹ́fà ẹlẹ́ẹ̀kejì, ó tún lọ sí Government College Ìbàdàn (Gci), ó sì parí ẹ̀kọ́ kíkà rẹ̀ ní ilé-e ẹ̀kọ́ Yaba Higher College ní Ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí nínú ẹ̀kọ́ olùkọ́ ..
wikipedia
yo
Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Olùkọ́ ní ilé-ẹ̀ọ́ rẹ̀ tí ó ti jáde tẹ́lẹ̀ (Government College, Ìbàdàn) tí ó sì ń kọ́ ni nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ àti ṣíṣàmúlò Ìṣirò (mechanics and Applied AcJesus)..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, ó yan iṣẹ́ ikọ́lé láàyò tí ó sì gb ilé-ẹ̀kọ́ ìkọ́lé Brixton lọ ní ìlú London..
wikipedia
yo
Kò pẹ́ púpọ̀ tí ó fi bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ ìkọ́lé tirẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1950s, ọ̀rẹ́ rẹ̀ bá sọ̀rọ̀ wípé kí ó dara pọ̀ mọ́ òṣèlú ní ọdún 1956, ó gba imọ̀ràn ọ̀rẹ́ rẹ̀, lọ́gán tí ó sì dara pọ̀ mọ́ òṣèlú ni ó wọlé ìdìbò tí ó sọọ́ di Mínísítà fún ètò Ọ̀gbìn apá Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.Akinola ni ó ṣe aṣojú fún ilẹ̀ Nàìjíríà níbi àpérò fún Óńjẹ àti nǹkan irè-oko(Food and Agriculture Organization) ní ilẹ̀ Adúláwọ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n tún fi ṣe ìgba-kejì Gíwá ilé-ẹ̀kọ́ fún ilé-ẹ̀kọ́ Federal University of Technology, Àkúrẹ́ ..
wikipedia
yo
Òun náà tún ní igbákejì Gíwá ilé-ẹ̀kọ́ University of Ìbàdàn àti University of Benin.Àwọn Ìmíràn sí àwọn ọjọ́aláìsí ní 1987àwọn Ọjọ́ìbí ní 1913..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re ni ó jẹ́ ẹgbẹ́ tó ó níṣe pẹ̀lú àṣà àti ẹnin ìbílẹ̀ t orùbà ilẹ̀ Nàìjíríà tí Olóyè Abraham Adesanya adarí rẹ̀, nígbà tí Olóyè Bola Ìgè nígbà ayé rẹ̀ sì jẹ́ igbá kejì rẹ̀..
wikipedia
yo
Àwọn tí wọ́n tún jọ jẹ́ olùdásílẹ̀ ni Olóyè Ọnàdògó, Olóyè Ruben Fárántí, Adégbọ̀n Adétákùún Láta Gki Dapó, Ọláníhun Àjàyí , Olú Fálae, Adébáyọ̀ Adéfaratì Adéfaratì Alhaji Íìyàn àti Ayọ̀ Adébanjo Adébanjo
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú Alliance for Democracy kalẹ̀ ní ọdún 1998, wọ́n lo àfojúsùn wọn ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re gẹ́gẹ́ bí àfojúsùn ìpolongo ìbò náà..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ẹgbẹ́ yí pàdánù ìdíje ìbò dìbò wáyé ní oṣù kẹta ọdún 2003, àwọn alátakò ọmọ ẹgbẹ́ náà lọ lọ́tọ̀, wọ́n sì dá Ẹgbẹ́ AD sílẹ̀, tí wọ́n sì fi Olóyè Bísí Aent ja Alága AD.Ní January 2006, àwọn jàndùkú olóṣèlú kọlu àwọn Akọ́wọ̀ọ́wó (convoy) adarí ẹgbẹ́ òṣèlú ní ìlú Òṣogbo tí ó jẹ́ Olú-Ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun .Ní ọdún 2008, wọ́n dá Afẹ́nifẹ́re Reneyípadà Group (alias ARG) kalẹ̀ pẹ̀lú àwọn èrò àti ìlépa láti so ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re papọ̀ kí ìyapa ó má sii mọ́ láàrín wọn, tí yóò sì tún máa jẹ́ ànfàní fún àwọn àgbà ẹgbẹ́ náà láti lè ma bá iṣẹ́ takun takun wọn lọ.Ní Oṣù Kọkànlá ọdún 2008, apá kan ẹgbẹ́ AAfẹ́nifẹ́re tí wọ́n fi faction of Afẹ́nifẹ́re in Ìjẹ̀bú Igbó , ní Ìpínl Ogun Ògùn Ògùn, èyí tí Olóyè Ayọ̀ Ayọ̀ Bánjọ ń darí rẹ̀, fi Olóyè Reuben Fásrántí jẹ gẹ́gẹ́ bí Alága ẹgbẹ́ tiwọn..
wikipedia
yo
Àwọn àgbà ARG ní èyí tí a ti rí Senator Ọláyíyí Dúrójayé , Olóyè Bísí Àkàndé , Wálé Ọ̀ṣun àti Yínká Òdúmákin fi léde wíé àwọn kò tẹ́wọ́ gba ìyànsípò náà wọlé ní tiwọn.Ní oṣù Kẹwàá ọdún 2009, agbẹnusọ fún ARG sọ̀rọ̀ nípa ètò yíyọ̀ ìkún pá lórí epo rọ̀bì lábẹ́lé ní ilẹ̀ Nàìjíríà.Bákan náà ni ẹgbẹ́ náà tún kan sárá sí Olóyè month, the ARG hailed the conviction of Chief Bode George àti àwọn márùún mìíràn fún akitiyan wọn láti fòpin sí ìwà àjẹbánu tó ti gbilẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà . Ọmọ Yorùbá ni wọ́n rí àwọn alátakò ìjọba lórí èrò wọn gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà tó tọ́ láti yí ìpinu ìjọba padà, tí ó sì ń fún àwọn ọmọ Yorùbá tí wọ́n wà nínú àjọ náà ní ìdánimọ̀ jákèjádò ilẹ̀ Nàìjíríà, ewé tí ó sì tún jẹ́ ọ̀nà kan láti tọ́jú ẹ̀yà Yorùbá lápapọ̀.Àríwísí àwọn kan wà lára àwọn ọmọ Yorùbá tí wọ́n rí ìdásílẹ̀ àwọn ẹgbẹ́ alátakò gẹ́gẹ́ bí ohun tó ohun tó léwu..
wikipedia
yo
Abu-Abdullah Adélabu tí ó jẹ́ onímọ̀ ẹ̀sìn Islam ṣàpèjúwe bá ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re gẹ́gẹ́ bí àkójọ àwọn ẹlẹ́yà-ó-mẹ̀yà tí wọ́n sì ń lo inọ̀ tara ẹnìkan, oní kèéta, tí wọn kò mọ̀ ju ìbàjẹ́ àwọn ẹlẹ́yà tó kú lọ..
wikipedia
yo
O se eyi nibi àpérò London Aafaf Africa College, Sheikh Adelabu, yí naa ni ẹni ti o jẹ oludasile the àwafaf Africa Society ni Ilu Lọndọnu.Awon itọka si awọn ọmọ Yoruba..
wikipedia
yo
Eric Alfred Leslie àtiẹ̀ tó gbajúmọ̀ bí Erik ṣátìe (; 17 May 1866 – 1 July 1925) jẹ́ ara Fránsì alásopọ̀ orin àti olórin.Àwọn ará Fránsì..
wikipedia
yo
Nnamdi kánú jẹ́ ajìjàngbara ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Bìrìms..
wikipedia
yo
Òun ni olùdásílẹ̀ àti adarí ẹgbẹ́ ajìjàǹgbara indigenous people of Biafra (Ipòb)..
wikipedia
yo
Ẹgbẹ́ yìí ló ń ìjọgbara òmìnira àti ìdásílẹ̀ orílẹ̀-èdè Biafra ..
wikipedia
yo
Nnamdi kánú náà olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ rédíò kan tí a mọ̀ sí Radio Biafra tó wà lórílẹ̀-èdè Bìrìtì..
wikipedia
yo
Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fi ṣìnkún òfin ìfipá-dá-bọlẹ̀ mú un ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹwàá ọdún 2015, wọ́n sì tì í mọ́lé fún ìgbà pípẹ́ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọ̀pọ̀ ilé-ẹjọ́ dájọ́ pé kí wọ́n dá a sílẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí kánú ń farahàn nílé ẹjọ́, iṣẹ́ ló máa ń múra bíi ọmọ Juu..
wikipedia
yo
Ó sọ nílé-ẹjọ́ pé òun nígbàgbọ́ ninu ẹ̀sìn àwọn Juu, òun sì ń rí ara òun gẹ́gẹ́ bíi ọmọ Juu..
wikipedia
yo
Ijoba orile-ede Naijiria da a sile lọ́jọ́ kejidinlogun osu kerin odun 2017 pelu béèlì pe ko gbodo fi orile-ede Naijiria sile, sugbon o sa lo gba ona ẹ̀bùrú si oke-okun.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Owó ni ohunkóhun tí àwọn ènìyàn kan bá gbà lágbègbè, ìlú tàbí orílẹ̀-èdè wọn láti máa fi ṣe káràkátà ọjà tàbí san gbèsè..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ohunkóhun tàbí àkọsílẹ̀ tó dájú tí gbogbo ènìyàn gbà láti máa fi san owó ọjà rírà, iṣẹ́ tí a ṣe fúnni tàbí san gbèsè àti owó-orí..
wikipedia
yo
Àwọn onímọ̀ ṣàlàyé pàtàkì owó gẹ́gẹ́ bí ohun tí a fi ń ṣe pàṣípàrọ̀ ọjà, nǹkan-ìdíye, nǹkan-ìdíyelé dukíàì, àti nǹkan ìpààlà iye ọjà..
wikipedia
yo
Ohunkóhun tí ó bá lè ṣe àwọn nǹkan wọ̀nyí ni a lè kà sí owó.Owó nínú ìtàn jẹ́ ohun tó tọ́ tí a fi ń ṣe ìdókòwò ọjà, àmọ́ ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ wípé owó láyé òde òní ni òní ètò tó dálé Àfia Money..
wikipedia
yo
(Ọwọ́ tí òun ti ale fojù rí bíi àgótì tàbí pélẹ̀ lọ́pọ̀ rọ́pò) Money, dá bí ṣọ̀wẹ̀ pàyé tàbí akosile fún ètò ìkó, kọ́ fíwà láàyè ara rẹ̀.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Diaen Carroll (; ti orúkọ àbísọ rẹ̀ n jẹ́ Carol Didian Johnson; July 17, 1935 – October 4, 2019) jẹ́ òṣèré., akọrin, aláṣọ-oge àti alákitiyan ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
O kọ́kọ́ di ìlúmọ̀ọ́ká láti inú àwọn fíìmù tó ní òṣèré Aláwọ̀-dúdú nínu bíi Carmen Jones (1954) àti Porgy and Bess (1959)..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1962, CarRoll gba ẹ̀bùn Tony bí òṣèré obìnrin tó dára jùlọ, obìnrin Aláwọ̀-dúdú àkọ́kọ́,fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré orí-ìtàgé Broadway nípa kíkọ orin No strings.àwọn ìtọ́ka síàwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Tdàdà jẹ ìlú kékeré kan ní ìhà ìwọ̀-oòrùn ti Cyprus..
wikipedia
yo
ó wà ní agbègbè Epardọ́250 PaFou, ní apá ìwọ̀-oòrùn ti orílẹ̀-èdè náà, 90km ìwọ̀-oòrùn ti olú-ìlú Nicosia àti 8 ibùsọ̀ sí àríwá ti paphos
wikipedia
yo
Gbàngàn pápá ìṣeré Tafawa Balewa, (TBS) jẹ́ ilẹ̀-ayẹyẹ tí ó tó Soṣíọ́lọ́jì ilẹ̀ bí ìwọ̀n Èyí tí a àkọ́kọ́ pè ní (Ilé Eré-ìje”) èyí tí ó wà ní Erékùṣù, EÌpínlẹ̀ Èkó .Ìtàn nípa gbàgàn yí ilé eré-ìje ìpínlẹ̀ Èkó tí ó ti di TBS báyìí ni ó jẹ́ pápá tí Ifẹ̀sin sáré ìdárayá tẹ́lẹ́ ní ìlú Èkó tí wọ́n sì ya apá ibì kan sọ́tọ̀ fún eré bọ́ọ́lù aláfẹsẹ̀gbá àti àyè kan fún eré bọ́ọ̀lù ẹlẹ́yin orí ilẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n yan ilẹ̀ náà fún àwọn ìjọba amúnisìn tí ó ń ṣàkóso lórí ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ nípa àṣẹ Ọba Dosunmu ní ọ̀dún 1859, tí ó sì padà mú ìdàgbàsókè bá agbègbè náà..
wikipedia
yo
Pápá náà ni ó o Ọ̀gágun Yakubu Gowon wó palẹ̀ tí ó sì yí padà sí gbàgàn Tafawa Balewa Square.Nígbà pápá yí wà l lójú iṣẹ́, àwọn ìla eré-ìje fún àwọn ẹṣin tí ó ń sáré níbẹ̀ tó méje sí mẹ́jọ, tí wọ́n sì gùn tó ibùsọ kan (1 mile).Ní ọdún 1960, wọ́n tún pàpà yí ṣe láti fi sàmì ayẹyẹ òmìnira orílẹ̀-èdè Nàìjíríà , tí wọ́n sì fa àsíá orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì amúnisìn wálé.Ibi tí gbàgàn yí wà gbàngàn TBS tí wọ́n kọ́ ní ọdún 1972 fìdí ti òpópónà Awólọ́wọ̀ Cable Street, ọ̀nà Fọ́ọ̀sì, ọ̀nà Catholic Mistree àti 26-storey independence building.gbàgàn yí bí ohun mánigbàgbé ẹnu àbáwọlé gbàgàn yí ni àwọn eré ẹ̀sìn mẹ́rin tí a ṣe ano rẹ̀ rè lọ́jọ́ pẹ̀lú àwọ̀ funfun báy, àti àwọn ẹyẹ àṣà méje tí a ṣe ọ̀nà wọn pẹ̀lú àwọ̀ pupa tí wọ́n ń rà bàbà lójú ọ̀run, tí àwọn iṣẹ́ẹ ọ̀nà yí sì ń tọ́ka sí àmì àmì àti iyì gẹ́gẹ́ gẹ́gẹ́ bí àkọmọ̀nà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Àwọn ohun àrà ọ̀tọ̀ tí ó jẹ́ mánigbàgbé ní 1(Àmì ìrántí Ogun Àgbáyé àkọ́kọ́ (i)..
wikipedia
yo
Ogun Àgbáyé ẹlẹ́kejì II àti àwọn tó fara káṣà nínú ogun abẹ́lé ilẹ̀ Nàìjíríà , tí ó sì tún dúró fún (The26-storey independence House), tí wọ́n kọ́ ní ọdún 1963, tí ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé tí ó ga jùlọ fún ìgbà pípẹ́ jùlọ ní ọ̀rẹ́-èdè Nàìjíríà.Àwọn ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀ gbàngàn yí gba àwọn ènìyàn tí ó tó ẹgbẹẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo..
wikipedia
yo
Àwọn ayé bí ibi ìtajà oríṣiríṣi, ilé ońjẹ, àyè Igbóọ́kọ̀ sí, àti ibi tí wọ́n ti ń ṣe tó ìwé ìrìnà lè sókè òkun.Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì tí ó ti wáyé níbẹ̀ rí lára àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ti wáyé tí ó kẹ́ mánigbàgbé ní ayẹyẹ ìgbòmìnira tí ó wáyé ní ọjọ́ kíní oṣù Kẹwàá, ọdún 1960 (1-10-1960), ti Olórí Mínísítà nígbà náà Tafawa Balewa, sì bá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ̀rọ̀..
wikipedia
yo
Lára rẹ̀ náà ni ayẹyẹ ọjọ́ òṣèlú àwa-ara wa (Democracy Day), àti àwọn mìíràn bí ìpàgọ́ orin àti ìpàgọ́ àti ìpéjọ pọ̀ àwọn ẹlẹ́sìn gbogbo.Àwọn ìtọ́ka sí Nigerian National Monument..
wikipedia
yo
Owó ẹyọ jẹ́ ohun àlùmọ́nì tí wọ́n ń lò láyé àtijọ́ gẹ́gẹ́ bí owó láti fi ṣe káràkátà láwùjọ Yorùbá àti ilẹ̀ Áfríkà lápapọ̀..
wikipedia
yo
LÁwùjọ Yorùbá, a máa ń rí owó ẹyọ gẹ́gẹ́ bí àmìn Ola tàbí aje..
wikipedia
yo