cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Àwọn Mìíràn á máa lọ̀ ọ́ gẹ́gẹ́ bí Ẹ̀gbá-Ọ̀run tàbí ẹ̀gbà-ọwọ́ láti fi ṣeSÒÒ..
wikipedia
yo
Awon babaláwo a tun maa lo o bi ọ̀pẹ̀lẹ̀ fun Ifa dida.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ilé Ìtàwé (ti a tun pe ni ile Ìtàwé CSS) jẹ ile kan ni Erékùsù Èkó, ó wà ní apá Ariwa-ila-oorun Òhùnà Gbota (Broad Street) ní òpópópópópó Odunlami..
wikipedia
yo
àwọn ilé iṣẹ́ tí ó n ya àwòrán ilẹ̀ tí à npè ní Godwin àti Hopwood fìdí ni ó ya àwòrán ilẹ̀ náà.Àwọn ìtọ́kasí erékùṣù Èkó..
wikipedia
yo
Àwọn òbí rẹ̀ ni Josiah Ogunpòọo Olayide (ti ẹgbẹ́ Ògbóni ipele gíga ni Ileṣa) ati Mariam Olayide (ọmọ Oni - ibatan Lisa ti Eti-Ooni ni Ìjẹṣà)..
wikipedia
yo
O fẹ́ Theresa Folashade Olayide (ọmọ Ikoli, ọmọ gbajumọ oloselu, olùfẹ́-orilẹede ati Oniroyin Ernest Seses Ikoli) ni 1961..
wikipedia
yo
O bi ọmọ mẹrin awon naa ni odunodun, Tokunbo, Oluwole, ati Olajide Olayide kẹkọọ ni ileile alako ṢỌ́Ọ̀ṢÌ Àpósítélì (Apostolic Church Primary School) ni Ileṣa ati kọlẹji awọn olukọ ti ijọba ni Ibadan ki o to tẹsiwaju lọ si Yunifasiti ti ilu Londonnu ni 1955, nibi ti o ti gba oye ba ninu Ẹkọ Oro - aje ni 1957..
wikipedia
yo
O lo si US nibi ti o ti gba oye MSc ati oye omowe ni Eko Oro-aje ajẹmọ́-ohun-ogbin- ati - ọsin..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ gíwá láàrín ọdún 1979 sí 1983, wọ́n sì yàn án láti du ipò fún sáà kejì kí ó tó kú lójijì ní March 1984..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó ti di àwọn ipò bí olùwádìí àti oludari mu, púpọ̀ gbajúmọ̀ ni Benin - Òwena River Basin Authority, Nifor, Yani, FAO (Àjọ Oúnjẹ àti ajẹmọ́-ọ̀gbìn-àti-ọ̀sìn ní Milan, Italo) àti Ẹ̀ka Ìṣàkóso Ètò ajẹmọ́-ohun- Ọ̀gbìn-àti-Ògun ti Ìjọba Àpapọ̀ Nàìjíríà (Federal Agricultural Coorating units Fácue.Olayide ti gbé ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ àpilẹ̀kọ jáde ni àwọn ìwé àtìgbàdégbà(Jónà) ti orílẹ̀èdè àti Jọ́nà Àgbáyé ajẹmọ́-ìmọ̀ báyé, èyí tí ó gbayì jù ni àpilẹ̀kọ rẹ̀ lórí “ìṣòro oúnjẹ orílẹ̀èdè Nàìjíríà” tí ó kà ní 1974 tí ó jáde nínú ìwé àtìgbàdégbà (Jónà) tí Ibùdó-ìmọ̀ Ìwádìí Ajẹmọ́ ìbáraẹnigbépọ̀ àti ọ̀rọ̀ Ajé ti Orílẹ̀èdè Nàìjíríà – (Nigerian Institute of Social and Economic Research (régé–
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó jẹ́ òǹkọ̀wé ogunlọ́gọ̀ àwọn ìwé ní ọ̀rọ̀ ajé, àtúpalẹ̀ àti tíọ́rì ọrọ-ajé àti ọrọ-ajé ajẹmọ́-ohun ọ̀gbìn àti ọ̀sìn..
wikipedia
yo
Eniola Ajao jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà , osere Tiata ni, ìlú Èkó ni ó ti wá, ó sì ti kópa nínu fíìmù tí ó lé ní márùndínlọ́gọ́rin ní iye..
wikipedia
yo
A dáa mọ́ gẹ́gẹ́bí òṣèré nípa bí ó ṣe ma ń fi ọgbọ́n-inú àti òye hàn nígbà tí ó bá ń kópa nínú eré .Ìgbé ayé rẹ̀ Eniola àti ìbejì rẹ̀ ni àbígbẹ̀yìn nínú àwọn ọmọ mẹ́fà tí àwọn òbí rẹ̀ bí..
wikipedia
yo
Nígbàtí ó ń dàgbà, Eniola lọ sí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ Maikeli mí ti Ijo Áńgílíkan, àti ilé-ẹ̀kọ́ girama tí àwọn ológun ní ìlú Ẹgún..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi Eniola ti sọ ọ, bi o tilẹ jẹ pe o wu u lati mu ori awọn obi rẹ wu, sibẹ, ifẹ inu rẹ ni lati jẹ oṣere tiata lati igba ewe rẹ..
wikipedia
yo
Eniola tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ nígbàtí ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ẹ̀rọ ní Yaba àti ilé-ìwé -Yunifásítì ìlú Èkó níbi tí ó ti gboyè nínú ìmọ̀ ìṣirò..
wikipedia
yo
bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ awuyewuye ti wáyé lórí ìbáṣepọ̀ tí ó wà láàrín Eniola àti Odunlade Adekola, Eniola ṣàlàyé pé kò sí ìbáṣepọ̀ mìíràn láàrín òun àti Odunlade Adekola lẹ́yìn tí iṣe.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ènìyàn aláàyè..
wikipedia
yo
Ibrahim Chatta ( tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlá Oṣù Kẹwàá ọdún 1970) jẹ́ gbajúgbajà olùdarí àti òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá láti Ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀ Nàìjíríà .ì-ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ Ibrahim Chatta kò fi bẹ́ẹ̀ kàwé púpọ̀..
wikipedia
yo
Ìpele kẹta Èkó sẹ́kọ́ndírì ni ó ti fi ẹ̀kọ́ kíkà sílẹ̀..
wikipedia
yo
Ó wá pápá kẹ́kọ̀ọ́ lórísisisi nípa eré sinimá àgbéléwò..
wikipedia
yo
Àkọsílẹ̀ kan sọ pé ó ti fìgbà kan ṣiṣẹ́ àpéròsoko.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Odunlade Adekola (ti a bi ni ojo kokanlelogbon osu kejila odun 1976) je osere sinima agbelewo, ọ̀rin, oludari ati olootu sinima agbelewo omo Yoruba lati ipinle Ekiti lorilẹ ede Naijiria..
wikipedia
yo
John Primary School, Abeokuta, o tẹsiwaju lẹ́kọ̀ọ́ rẹ ní St..
wikipedia
yo
Ibe ni o ti gba iwe - eri West African School Certificate Examination (WAWA), ki o to kawe gboye eri diploma ni ile eko giga Moshood Abiola Polytechnic..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2018, ó tún kàwé gboyè Middlors of Business Administration ní Ifáfitì ìjọba àpapọ̀ ní Ìpínlẹ̀ Èkó, University of Lagos.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Yemi Sodiimu ni won bi ni kokandinlogbon osu kinni, odun 1960 ( January 29, 1960) ni ilu Abeokuta ni orile-ede a Naijiria je elere ori itage, atọ́kùn eto, oludari ati olùgbéré jade.ìgbòkègbodò aye re won bi ni ilu Abeokuta, ti o je olu ilu ipinle Ogun ni apa iwo Oorun orile-ede Naijiria.O lo igba ewe re ni ilu Abeokuta Abeokuta I ààfin oba Aláké ilẹ̀ Egba ni bi bi ti o ti ni ami Yoruba.. Asa Yorùbá..
wikipedia
yo
Ó le sí ilé-ẹ̀kọ́ kọ́wńbá Awólọ́wọ́ University níbi tí ó rí gba ìwé ẹ̀rí Bachelor of Arts (B.A.) , nínú ìmọ̀ ọ̀nà ìṣeré ìtàgé ( Dramatic art) , lẹ́yìn èyí ni ó tẹ̀ síwájú ní Fásitì Ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí Master of Arts (M.A.) Nínú ìmọ̀ Mass Communication.Iṣẹ́ òòjọ́ rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 1976, tí ó aì kópa tó lààmì laka nínú eré orí ìtàgé tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ Village Head Master.Ó di ìlúmọ̀ọká pẹ̀lú ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Olú ẹ̀dá ìtàn, ó tún jẹ́ Olú Ẹ Ẹ̀dà ìtàn nínú eré orí ìtàgé tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ ''' lékú''' gẹ́gẹ́ bí Àjàní nínú eré yí.Tunde Kelani ṣe adarí yà eré orí ìtàgé rẹ̀ Village Head Master that featured Victor Ọláó Ọlá Ó Lèkú (1997) Láti ọwọ́ Tunde Tunde Kelani tí Olúwa ní Ilẹ̀ Ṣaworo Idẹ tí Kúnlé Afọláyan àti Peter Fátómil Ayọ̀ ni Mofẹ́ kọ́ẹ́ tún le wo tó tó àwọn òṣèré ilé _*I
wikipedia
yo
{{Infobox Golfer| name = Tiger Woods| Image = Tiger Woods in May 2019.jpg| Caption = Woods at the White House in May 2019| Funame = Eldrick Tont Woods| Nickname = Tiger| Birthdate = ↑ Birthplace = Cypress, California| Death23date = ↑ Deathplace =| Height = 6 ft 1 in National| Weight = Aroko | Nationality = ↑ Residence Island Island Island, Spouse| Spouse ↑ Partner = ↑ Children = 2| College = Oyin University(Two 2015) Year| Year = Mo’’ rẹ̀ ↑ Tour = p tour (joined 1996) Prowins 15 108 108 Elàdàbà Tont “Tiger” Woods (Ọjọ́ìbí December 30, 1975) jẹ́ àgbà gọ́ọ̀fu tó peregedé ará Amẹ́ríkà, ó wà ní ipò kejì nínú àtọ̀ àwọn ọkùnrin tó tayọ jùlọ tó gba ìfẹ́-ẹ̀yẹ Goofu àti ẹni tí ó ti mókè jùlọ nínú p tour náà ó ní AAṣeyọrí nínú àwọn àgbà nínú àwọn àgbà ilẹ̀ Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Woods tún jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú àwọn àgbà Goofu tó peregedé jùlọ àti ìkan pàtàkì nínu àwọn eléré-ìdárayá tó gbajúmọ̀ jùlọ lágbàáyé.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ará Américo ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Sola Kosoko-asápamọ́ (tí a bí ní ọjọ́ keje Oṣù Kínní Ọdún Born 1976), jẹ́ òṣèrébìnrin àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ Yorùbá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ bíbí àgbà òṣèré Jide Kosoko.Ìgbé-ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ kíkà rẹ̀sola Kosoko jẹ́ ó ọmọbabìnrin ìsàlẹ̀ ẹ̀kọ́..
wikipedia
yo
Ni ibẹrẹ aye rẹ, o lọ si ile-iwe akobere Methodist Primary School, Yaba ni Ipinle Eko..
wikipedia
yo
Yaba kan náà ló ti kàwé sekondiri kí ó tó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ifáfitì Olabisi Onabanjo níbi tí ó ti kàwé gboyè nípa ìmọ̀ ÀYÍKÁ (sociology)..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìdílé Ọba ni Sola Kosoko ti wá, bàbá rẹ̀, Jide Kosoko jẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá gbégbékan, èyí ran an lọ́wọ́ lọ́lọ́pọ̀ nígbà tí ó dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ tíátà ní kérin tí ó pari ẹ̀kọ́ Sekondiri kí ó tó di ìlúmọ̀ọ́ká dún 1999 nínú sinimá kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ “ọmọ olóríire mọ́ ó gúnlẹ̀ orúkọ tí bàbá rẹ̀ ti ní pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ bàbá rẹ̀.Ó fẹ́ ọkọ rẹ̀, Abiodun a ní ọdún 2012, wọ́n sí bímọ méjì méjì..
wikipedia
yo
Olóyè Làdi Aríyíbí Àkànjí Adédibú ni a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlógun oṣù Kẹwàá, ọdún1927 (24-1927-1927 sí 11- ) jẹ́ alẹ́nulọ agbára alẹ́nulọ́rọ̀, apàṣẹ-wàà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ..
wikipedia
yo
Oloye Olusegun Obasanjo ṣapejuwe rẹ̀ bí "Bàbá" fún ẹgbẹ́ òṣèlú "PDP". àti ebi rẹa bí Olóyè Adédibú ní agbègbè Ọjà Ọba ní ìlú Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ oyè láti ìdílé Ọba Olúpòyí.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olóṣèlú Adédibú dára pọ̀ mọ́ ìṣèlú ní ọdún 1950, nígbà tí ó di ọmọ ẹgbẹ́ Peole's Party, tí ó sì dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèl Action Group lábẹ́ Olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ ..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn náà, ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèlú National Party of Nigeria (NPN) , ẹgbẹ́ tí ọ̀gbẹ́ni Adisa Akinloyè àti Richard AkinJide ..
wikipedia
yo
Ó di onípò pàtàkì nínú òṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà ní àkókò ìjọba ológun Ọ̀yángùn Ibrahim Babangida, lákòókò yí ni ẹgbẹ́ òṣèlú NPN lo àǹfàní ètò ìdìbò ojúmitó (open ballot) láti ṣe màdàrú..
wikipedia
yo
ọ̀nà tí a lè gbà ṣàpèjúwe ìlànà òṣèlú tirẹ̀ ní lílo àwọn ọmọ gànfẹ̀ , àti fífi ipá mú ọmọ ayọ̀ rẹ̀ tàbí alátakò rẹ̀ ṣe oun tí ó bá fẹ́ tí ó sì ma ń mú jàgídí-jàgan lọ́wọ́ lọ́pọ̀ ìgbà..
wikipedia
yo
a gbọ́ wípé kò fẹ́rẹ̀ sí olóṣèlú kan tí ó goróyè ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí kò gbàṣẹ gbòntẹ̀ Adédibú kí ó tó dépò àṣẹ..
wikipedia
yo
Èyí ló fàá tí wọ́n fi n pèé ní òpómúléró òṣèlú ilẹ̀ Ìbàdàn .Wọ́n yan ọmọ rẹ̀ kan , Kamokirudeen Adékúnlé Adédibú , gẹ́gẹ́ bí aṣojú -ṣòfin sílé Aṣòfin àgbà fún ẹkùn Ọ̀yọ́ South ní oṣùkerín ọdún 2007 .Senator Teslim Folarin , í wọ́n dìbò yàn sílé Aṣòfin àgbà gẹ́gẹ́ bí Senator fún ẹkùn Adé-gbùngbùn Ọ̀yọ́ (Oyo Central) ni ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ lẹ́yìn Adédibú .Ẹ̀wẹ̀, olóyẹraheed Láìdáláre Lájà tí ó jẹ́ gómìnà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní oṣù Karùún ọdún 2003, náà tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹ̀kọ́ṣẹ́ lẹ́yìn rẹ̀..
wikipedia
yo
Àmọ́ oun ati Adédibú padà di oje ọ̀rọ̀ àti ojú tí wọ́n kìí fẹ́ rí ara wọn lórí tani yóò yàn sí.Awon ipò Komisona ní ọdún 2004.Iku ReAdédibú kù ní Ọjọ́ kọkànlá Oṣù kẹfà, ọdún 2008 sí ilé ìwòsàn University College tí ó wà ní ìlú Ibadan , nígbà tí ó wà ní ipò ẹbí ti ilé Ibadan gẹ́gẹ́ gẹ́gẹ́ bí ipò tí ẹbí rẹ̀ wà sí ti Òluwèlu ti ilé Ibadan.Awon ìtọ́kasí̀ àwọn ọkò ní 2008àwọn Ọjọ́ìbí ni 1928..
wikipedia
yo
Ìpín Àgbádárìgì ní ìpín kan lára ẹ̀ka tí ó ń ṣe àkóso ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìtàn rẹ̀ Ìpín àgbádárìgì kópa tó lọ́ọ̀rìn nígbà tí a bá ń ṣe àgbéyẹ̀wò nínú ìtàn ilẹ̀ Olómìnira Nàìjíríà àti Europe..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí Agbadarigi ṣe jẹ́ agbègbè tí wọ́n ti kó ẹrù tí ó pọ̀ jùlọ nínú iṣẹ́ òwò ẹrú lágbàáyé, ṣáájú ìjẹ gàba àwọn Eebo amúnisìn..
wikipedia
yo
Ìpín Àgbádárìgì tún jẹ́ ibi tí àwọn Èèbó Aláwọ̀ Fundun ti kọ́kọ́ polongo ẹ̀sìn Kristẹni ní ikẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 1842..
wikipedia
yo
Mowọ jẹ́ ìlú kan ní Agbadarigi, Ìpínlẹ̀ Èkó , ní apá ìwọ̀ ilẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìlú náà kò jìnà púpọ̀ sí agbègbè ìloro ibodè Seme..
wikipedia
yo
Àwọn tí wọ́n tó ìdá 78,897, àwọn olùgbé tí ó ń gbé níbẹ̀ lọ..
wikipedia
yo
púpọ̀ nínú àwọn olùgbé ìlú yĩ ni wọ́n jẹ́ olùṣòwò àti olùtajà tí wọ́n sì ma ń lé láti ra àwọn ọjà títà wọ́n ní Seme.Àgbò wípé àwọn ilé tí wọ́n tó ìdá ọgọfa (600) tí ó wà ní orí ilẹ̀ tí ó tó àádóje (65) hẹ́kítà ní ilé-iṣẹ́ àjọ ọlọ́pàá ilẹ̀ Nàìjíríà bi wó lulẹ̀ láti lè kọ́ ilégbèé àwọn ọlọ́pàá sí ní ọdún 2013 .Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Adé olùfèsì (orúkọ ibi Adé Abayomi olùfékọ́; Ọjọ́ìbí, 1980), jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tí ìmọ̀ rẹ̀ jinlẹ̀, ẹnití iṣẹ́ rẹ̀ ní ìmọ̀ ẹ̀dá tayọ ní Ìgbìmọ̀ Àwọn tó ń pero lórí kò èyí tí ó le kì jẹ́ ọrọ̀ lọ dédé lọ..
wikipedia
yo
Adé olùfékọ́ jẹ́ olùkọkẹ́kọ tí ó kọ́ ẹ̀kọ́ lórí ìmọ̀ tẹ̀Ódijì láti orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà, ó tún jẹ́ olùdarí iṣẹ́ àti Alápèrò kãkiri àgbálá aiyé, Ọmọ bíbí Ìjẹ̀bú..
wikipedia
yo
ìkóríta ibití ìmọ̀ rẹ̀ ni oríṣilọ́pọ̀ ìrírí ìmọ̀ dé ni ó jẹ́ kí ó dá pinnu ní ọdún 2007 láti dá ilé iṣẹ́ “wiwo ajọṣepọ” (Visual Collaborative), ibíyí jẹ ojú Apejọ fún àwọn oníìmọ̀ ènìyàn àti ìṣẹ̀dásílẹ̀ ..
wikipedia
yo
Ó jẹ ọ̀gá pátátata nínú àwọn tí ó ṣètò ilọ́dẹ̀dẹ̀ ìdarí ní àpéjọ yí ..
wikipedia
yo
O tun je Konsultántí ni imo ti o to eniyan si ona to pe ni IBMkasí.Awon Olukọwe ara Naijiri ara Naijiria..
wikipedia
yo
Eré ìdárayá jẹ́ àṣà àti ọ̀nà ìdárayá jákè-jádò ilẹ̀ Yorùbá nígbà tí ọwọ́ bá dilẹ̀..
wikipedia
yo
Yorùbá bọ̀ wọn ni “Ohun gbogbo ni ìgbà àti àkókò nbẹ fún”
wikipedia
yo
Ṣugbọn bí wọ́n ti fẹ́ràn iṣẹ́ tó, ó ní àwọn àkókò tí wọ́n máa ń fi sílẹ̀ fún eré ṣíṣe ninu ọjọ́ kọ̀ọ̀kan..
wikipedia
yo
Eyi fi han pé kii ṣe àwọn òyìnbó ni o mu ere idaraya dé ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Yorùbá ka eré ìdárayá si eré pàtàkì nítorí ó yẹ wọ́n pé ipa ti ó gbópọn ni èrè ìdárayá nkó nínú àlàáfíà ara àti ẹ̀mí gígùn..
wikipedia
yo
Bí eré ìdárayá ṣe wà fún àwọn ọmọ ọwọ́ àti ọmọ irinṣẹ́ náà ni ó wà fún ọmọdé àti àgbàlagbà..
wikipedia
yo
Oríṣìíríṣìí ni eré ìdárayá tí a máa ń ṣe nílẹ̀ Yorùbá, púpọ̀ sì ni kò mú agbára dání nítorí lẹ́yìn iṣẹ́ agbára ni Yorùbá ńṣe wọn..
wikipedia
yo
Awon ere idaraya kan wa fun ilera, lati mu ki ara làágùn..
wikipedia
yo
Àwọn mìíràn wà fún ìnàjú, àwọn kan wà gẹ́gẹ́ bíi amúṣẹ́yá..
wikipedia
yo
Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìsọ̀rí mìíràn wà fún dídá ọ̀pọ̀lọpọ̀ laraya..
wikipedia
yo
Lára eré ìdárayá Yorùbá ni eré ayò, àrin, Òkòtó, ìjàkadì, kànnàkànnà, eré òṣùpá, eré Àlọ́, Adédélé, Kí-ní-n-lẹ̀jẹ́ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Ayọ̀ títaayó títà jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn eré ilẹ̀ Yorùbá tí wọ́n máa fi dárayá l'ẹhìn iṣẹ́ òòjọ́ wọn..
wikipedia
yo
Ere abele ti ko gba agbara ni ere ayo, bẹẹ si ni ori ìjókòó ni won ti nta a..
wikipedia
yo
Ọ̀sán tàbí ìrọ̀lẹ́ ni wọ́n ń ta ayọ̀ ní ìgbà tí wọ́n bá ṣíwọ́ oko wá sí ilé.“Ère l'á ńfi ọmọ ayò ṣe”
wikipedia
yo
Ó sì jásí pé eré ayọ̀ kìí ṣe nkan ìjà tàbí ohun tí ó lè mú ìkùnsínú wá..
wikipedia
yo
Bí a bá sì tún f’etí sí àwọn àgbàlábá nígbàmíràn, a ó gbọ́ tí wọ́n nsọ báyĩ pé "t'ọ́mọdé t'àgbà ni iyọ̀ mọ́ ọmọ ayò..
wikipedia
yo
Ọpọ́n ayọ̀ yóò sì wà láàrín wọn.Ọpọ́n ayọ̀ jẹ́ ohun èlò ayọ̀ títà tí ó ní ihò méjìlá tí à ń dá ọmọ ayọ̀ sí, tí mẹ́fà-mẹ́fà kọjú sí ara wọn..
wikipedia
yo
Ihò kọ̀ọ̀kan tó le yìí a sì máa wà ní apá ọ̀tún àti apá òsì ọpọ́n náà..
wikipedia
yo
Ihò meji yi wà fún lílò àwọn ọ̀táyó láti tọ́jú ayọ̀ tí wọ́n bá jẹ sí..
wikipedia
yo
Nígbà mìíràn, àwọn ènìyàn máa ń gbẹ́ ihò sí orí ilẹ̀ tí yóò dúró gẹ́gẹ́ bí ọpọ́n ayọ̀, ṣùgbọ́n ohun tí a kàn nípa ní ihò méjìlá ojú ọpọ́n ayọ̀..
wikipedia
yo
Bí ọpọ́n ayò báwa bí kò bá sí ọmọ ayò, ayò kò sé ta rárá..
wikipedia
yo
Ìyẹn túmọ̀ sí pé àyọ̀títà kò lè rọrùn láìsí eso ayọ̀ tí a tún mọ̀ sí ṣẹ́yọ.Ọmọ ayọ̀ jẹ́ kóró inú èso igi kan báyĩ, èso yìí dán lára púpọ̀, ó sì le kóró kóró, ara rẹ̀ yóò má yó korò..
wikipedia
yo
Èyí jásí pé ọmọ ayọ̀ mejidinlaadọta ní ḿbẹ l'ójú ọpọ́n ayọ̀, àwọn ọ̀táyó yóò sì pín l'àárín ara wọn dọ́gbadọ́gba..
wikipedia
yo
Ọmọ ayò gbọdọ̀ pẹ́ kí èrè ayọ̀ tóó bẹ̀rẹ̀.Ṣùgbọ́n bí a kò bá wá rí àdán, a máa fòsẹ̀ sébọ́..
wikipedia
yo
Bí òùngbẹ ayọ̀ bá ńgbé àwọn ènìyàn tí nwọn kò sì lè rí ọ̀kan nínú àwọn ohun tí a fi nṣe ọmọ ayò, a máa ń lo òkúta wẹ́wẹ́ láti fi dípò ọmọ ayò..
wikipedia
yo
A sì ń lọ kọ̀rọ̀ iṣin pẹ̀lú.Èèwọ̀ ni kìí á ta ayò ní alẹ́ àti àárọ̀ kùtùkùtù..
wikipedia
yo
Ó máa ń pani lẹ́rìn-ín, a ó gbé apá, a ó gbé ẹsẹ̀, ara wa yóo sì yá gágá..
wikipedia
yo
Èrè ayọ̀ a máa mú ni ronú jinlẹ̀, tí ó sì lè mú kí ọpọlọ ẹni gbòòrò sí i..
wikipedia
yo
Ó nmú ni ronú kíákíá, ó sì mú kí ojú wa ríran síwájú sí.Èrè ãrínbí àwọn ènìyàn bá fẹ́ ta ãrín tàbí ṣe eré ãrín, nwọn a wá èso tí a npè ní Seeãrín lọ sí inú igbó..
wikipedia
yo
Ènìyàn mẹ́ta ní nta irú ãrín yí lẹ́ẹ̀kannáà.Kí ọmọdé tàbí àwọn géńdé tó pàdé níbi eré ãrín, nwọn a ti wọ ihò tí kò ju bí ìsun méjì tàbí mẹ́ta, wọ́n yóò tẹ ẹni Pàkìtí lé ihò náà lórí..
wikipedia
yo
Bákannáà ni nwọn ó sì ti wa ãrín bí mẹ́fà mẹ́fà tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ dání..
wikipedia
yo
Àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yóò ta ãrín wọn sínú ihò tí a tẹ́ ẹni sí lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo..
wikipedia
yo
Ẹnikẹ́ni tí ãrín rẹ̀ bá jáde láti inú ihò yóò san ãrín mìíràn fún ẹni tí ó ní ãrín tó lé e síta..
wikipedia
yo
Ṣugbọn bí arin àwọn mejeeji tí ó ṣẹ́kù si'nu ihò bá túká lẹ́ẹ̀kannáà á jẹ́’pé àwọn méjèèjì náà ta omi..
wikipedia
yo
Ẹni tí àrin rẹ̀ bá sì gbèyìn sínú ihò ni ó borí.ànfàní tó wà lára eré àrin pọ̀ ìṣeú rere, lára ẹ̀ ni pé, ó ńkọ ní l'ékọ́ láti mọ bí a ti nf'ojú sun ohun òkèèrè..
wikipedia
yo
Ó ńfún ojú wa l’àgbàrá láti ríran dáradára àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Bójú bojúbọ̀ọ́jú bọ̀ọ́jújẹ́ ọ̀kan lára erémọdé tí a máa nfi ọ̀yàyà ṣe..
wikipedia
yo
Ènìyàn bí mẹ́jọ tàbí mẹ́wá lè ṣe eré bọ̀ọ́jú bọ̀ọ́jú.Nínú ẹrẹ̀ bọ̀ọ́jú bọ̀ọ́jú a máa ń bo ènìyàn kan lójú..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí a bá bọ ẹnìkan lójú tán, àwọn ọmọde yòókù yóo lọ sá pamọ́..
wikipedia
yo
Nígbà tí nwọ́n bá nfi ara pamọ́ báyĩ ẹni t'ó ndijú yóò máa kọrin pé “Bo ojú bò ó ojú o”..
wikipedia
yo
Nígbà tí a bá ti ṣí aṣọ lójú ẹni náà tán, kò ní mọ ibi tí yóo lọ rárá; lẹ́hìn ìgbà pípẹ́ tabi díẹ̀, ó lè lọ rí ẹnìkan níbi tí ó sá pamọ́ sí..
wikipedia
yo
wípé ó rí ẹni yí kò sọ pé kí ọwọ́ rẹ̀ tẹ̀ ẹ́, nítorí ní rírí tí ó ti rí i yẹn, ẹni tí a rí náà kò ní dúró rárá, yóò yára bá ẹsẹ̀ rẹ̀ ṣòro láti sálọ..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n ti ẹni tí ó nwá wọn kiri yí bá ṣe rí ẹnìkan mú, ẹni tí ó bá mú ni yóò ṣe èrè bọ̀ọ́jú bọ̀ọ́jú mìíràn.Nígbà tí ẹrẹ̀ ọjọ́ yí bá fẹ́ ká’ṣẹ́ nílẹ̀, ara ẹni tí nwọ́n bá ti mú yóò wá kan gọ́gọ̀, òun náà yóò sì gbìyànjú gidigidi láti rí ẹnìkan mú nítorí yóò máa bẹ̀rù kí ẹrẹ̀ má baà kú mọ́ òun lórí..
wikipedia
yo
Awon asa ati orisa ile Yoruba lati owo olu Dáramọ́lá ati Adebayo Jẹ́jẹ́.2..
wikipedia
yo
Ẹ̀kọ́ Èdè Yorùbá Òde Òní láti ọwọ́ ẹgbẹ́ akọ́mọlédè Yorùbá.3..
wikipedia
yo
Monkáen káenkoon jẹ olorin ọmọ orilẹ-ede Thaláǹdì.Àwọn akọrin ara Thalá..
wikipedia
yo
Tai oraThai je olorin omo orile-ede Thaláǹdì.Àwọn akọrin ara Táílá..
wikipedia
yo