cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Maria Ayen Mayarsirísifirst Lady of South Sudanàwùjọtí a se iṣẹ́ ọfiisi August , 2005Ààrẹsalva Kiir Mayarsirísifirst Lady of South Sudanàwùjọtí a se iṣẹ́ ọfiisi August , 2005ṣáájú nípasẹ̀John Gamúnikúnàwọn alaye ara enia bi1951 oloselu–SECmo (s)sal Kiir Kiir Mayar.. | wikipedia | yo |
Coretta Scott King (April 27, 1927 – January 30, 2006) jẹ́ Olùkọ̀wé, alákitiyan, aṣíwájú fún àwọn ètò aráàlú ará Amẹ́ríkà, àti ìyàwó Martin Luther King Jr... | wikipedia | yo |
Ó ṣakitiyan fún ìbáradọ́gba àwọn ọmọ African-American, ó ṣe aṣíwájú fún Civil Rights Movement ní 1960s.. | wikipedia | yo |
King tún jẹ́ akọrin tó lo orin nínu iṣẹ́ rẹ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú.. | wikipedia | yo |
King ba ọkọ rẹ̀ pàdé Nomigba tí wọ́n Jọ wà ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì ní Boston.Ìtọ́kasí ará Américo ọmọ Áfríkà Ameririco Kanka Adi Ara Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Charleston ní ìlú tótipẹ́lo àti ìlú tótóbijùlọ ní Ìpínlẹ̀ South Carolina ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà àti Ìbújóòkó ìjọba Ìbí́ Charleston:Ìtọ́kasí àwọn ìlú ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Isegbéraga awon alawofunfun tabi isegbéraga awon oyinbo ni Sistemu isejoba awon ti won pe ara won ni alawofunfun/oyinbo ti won si fi okan si.. | wikipedia | yo |
Yunifásítì ẹ̀kọ́ ọ̀gbìn ti ìjọba àpapọ̀, Abeokuta (FUNAAB)ìtàn-akọọlẹ Yunifasiti Èkó ọ̀gbìn ti ìjọba àpapọ̀ tí o wà ní ìlú Abeokuta ní ìpínlẹ̀ Ògùn ní ìjọba àpapọ̀ da sílẹ̀ ní ọjọ́ kini oṣù kini ọdún 1988 (1 January 1988).. | wikipedia | yo |
Ijoba apapo pa Yunifasiti imo ero merin papo mo awon Yunifasiti merin miran ni odun 1984 ki o to di wipe won ni ki won da duro.. | wikipedia | yo |
Eleyí ló fa ìdásílẹ̀ Yunifásítì Èkó ọ̀gbìn méjì, ọ̀kan sí ìlú Abeokuta àti èkejì sí ìlú wóngùn.. | wikipedia | yo |
Ni ojo kan naa yi ni ijoba yan ojogbon Nurudeen Olorun-nimbe Adedipe gege bi igbakeji alase akoko ti Yunifasiti eko ogbin Abeokuta.. | wikipedia | yo |
Ọ̀jọ̀gbọ́n Adedipe dawole ise ní pẹrẹwu lábẹ́ àṣẹ ní ọjọ́ kejìdín-lọ́gbọ̀n oṣù kinni ọdún 1988 (28 January 1988).. | wikipedia | yo |
Fun opolopo odun ni won ti sesi gba ojo ti ojogbon Adedipe dawole ise gege bi ojo idasile.. | wikipedia | yo |
Nígbàtí tí wọ́n ṣe àtúnyẹ̀wò sí òfin tí ó dá Yunifásítì yí sílẹ̀, àjọ ìgbìmọ̀ ṣe ìpinnu nínú ìpàdé kẹtàlé-ìta rẹ̀ (53 Statory Council TT) ní Oṣù Kẹfà Ọdún 2010 (June 2010) dá ọjọ́ ìdásílẹ̀ padà sí ọjọ́ Kínní Oṣù Kínní ọdún 1988 (1 January 1988) gẹ́gẹ́ bi òfin tí ó dá Yunifásítì Èkó ọ̀gbìn yí ṣe là sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Kí ó tó di wípé Yunifásítì Èkó ọ̀gbìn Abeokuta (FUNAAB) wáyé, ìjọba ti kọ́kọ́ ṣe ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti ìmọ̀ ẹ̀rọ, Abeokuta ní ọdún 1983.. | wikipedia | yo |
Sugbon nigba ti o di odun 1984 ni ijoba pa ile eko giga yi po mo Yunifasiti eko (University of Lagos) ti won si yi oruko re pada si ile-iwe giga ti eko ijinle ati ti imo ero ti ilu Abeokuta (College of Science and Technology, Abeokuta) (COSTAb) ki o to di wipe o da duro ni osu kini odun 1988.. | wikipedia | yo |
Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì yí bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ikọ̀ ẹ̀kọ́ ní gbọ̀ngàn ilé-ìwé Abeokuta girama ti àtijọ́ tí ó wà ní ìgboro ìsàlẹ̀-ìgbẹ̀hìn.. | wikipedia | yo |
Yunifasiti yi pari ìsìpo pada rẹ lọ si ibi ti yi o wa titi láìyẹsẹ̀ ni opopona alabata ni ọdun 1997.. | wikipedia | yo |
Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, ẹ̀ka ìkó ẹ̀kọ́ márùn-ún ni wọ́n kọ́kọ́ fi lélẹ̀ ní Yunifásítì yí ní oṣù kẹwàá ọdún 1988.. | wikipedia | yo |
ilé-ẹ̀kọ́ Federal ti ọ̀gbìn Abeokuta ọjọ́ ilé-oye ile-oorun Naijiriàwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Tinubu (ti a n pe ni Ọ̀wọ́n Gbọ̀ngàn Ominira tẹ́lẹ̀ ri), jẹ́ ọ̀wọ́n manigbagbe ti o wa ni opopona gbooro (Broad Street), ni Erekusu Eko (Lagos Island), ni Ipinle Eko, ni orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ní ìgbà kan rí, ìta Tinúbú ni a npè ní ìítí ìyáàfin Efunroye Tinúbú tí ó jẹ́ oníṣòwò ẹrú àti gbajúgbajà oníṣòwò, kí ó tó di pé a yí orúkọ rẹ̀ padà sí ọ̀wọ́n gbọ́gàn òmìnira láti ọwọ́ àwọn olùdarí ètò ìṣèjoba ara ẹni àkọ́kọ́ ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, lẹ́yìn èyí ni a tún wá yí orúkọ rẹ̀ padà sí ọ̀wọ̀n gbọ̀ngàn Tinubu. Gbọ̀ngàn yíì jẹ́ onígun-mẹ́rin tí a fi irin ṣe odi yìí káàkiri, ó sì ní orísun omi méjì tí ó nfan omi sí àwọn òdòdó àti àwọn igi ilẹ̀ olóoru tí ó wà nínú rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Eré Ìyáàfin Tinubu tí ó ga tó ìwọ̀n ènìyàn wà nínú gbọ̀ngàn yìí ó sì dúró lórí kárí kan.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Immanuẹlla Samueli (a bi ni ọjọ́ keji-le-logun oṣu keje, ọdún 2010) orúkọ inagijẹ ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn mo si ni Emmanuella ó sì jẹ́ ọmọde ó Ddẹ p'òṣónú lori ikanni Mark Angel lórí ẹ̀rọ alátagbà YouTube.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, ní ikanni ìtara Mark Angel lórí ẹ̀rọ Aláta YouTube di àkókò irú rẹ̀ tí ó jẹ́ wípé ọmọ Nàìjíríà ló nií òun sí ní àkókò tí yóó ní àwọn olólùfẹ́ tí ó tó milionu kan ní Iye.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ Immanu Samuẹli jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ ìpínlẹ̀ ní apá iha ila-oorun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
A bi ni Port Harcourt ni Ipinle Rivers .Iṣẹ Immanu bẹrẹ iṣẹ awada nigbati o pe ọmọ ọdun marun.. | wikipedia | yo |
Yakub Abiodun Balogun (ti a bi ni ojo karun-un osu karun odun 1951) je omo orile-ede Naijiria ti o mo nipa eto oro-aje, oludari eto isejoba, asofin ni ilée asoju-sofin kéreré ni orile-ede Naijiria, ti o n ṣoju fun Lagos Island Federal Constituiyì II, Ipinle Eko, South-West Nigeria ati olutọju asoju ti Ipinle Eko nigba kan ri.ibẹrẹ aye re a bi Balogun Yakub ni ojo karun-un, osu karun-un, odun 1951 ni Lagos Island.. | wikipedia | yo |
Ile-iwe FaŽil-Omar Ahyyà ni Ipinle Eko ni o lo ki o to lo ile-iwe girama ti Ansar-Ud-deen ni Surulere, amo o gba iwe-ẹri waEC ni Ahmadi College, ni Agege.. | wikipedia | yo |
Ati Masters ninu ẹkọ Economics ni University of Ibadan ni ọdun 1976 ati 1983 ki o to lo Royal Institute of Public Administration nibi ti o ti gb a iwe-ẹri Public Administration ni ọdun 1996.Iṣẹ ijọba o dara pọ mọ iṣẹ ijọba ti ipinlẹ Eko ni ọdun 1977 gege bii Akowe Kekere ni ẹka to n ri si idagbasoke ati ifilelẹ eto aje.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1990, o lọ sipo oludarikeji fun awon ori-ori, ni ajo to n ri si eto-isuna.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tó ti sin ní onírúurú ọ̀nà, wọ́n yàn án sípò akọ̀wé àgbà ní àjọ tó ń rí sí ètò ìṣúná, ní ọdún 1997.. | wikipedia | yo |
Ó sì wà nípò yìí títí wọ́n tún fi yàn án sípò olórí àwọn òṣìṣẹ́, ní ọdún 1999, lábẹ́ ìṣèjọba Olóyè Bọ́lá Tinúbú, tó fìgbà kan jẹ́ gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó, àti adarí àgbà ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC).. | wikipedia | yo |
Ni osu kaun-un, odun 2010, o fẹyìntì nídìí ise ijoba lati wo egbe oselu.Iṣẹ oselu ni osu kerin, odun 2011, Olayemi fun ipo ijoba ibile ni ipinle re, Lagos Island Federal Constituiyì II, ti o si wole.. | wikipedia | yo |
Balogun jẹ́rìí si iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi ọmọ ẹgbẹ ile igbimọ aṣofin, to duro fun, Lagos Island Federal Constituiyì II, Lagos State, ni ọjọ aje, ojo kẹfa, oṣu kẹfa, ọdun 2011.Awon itọkasi awon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1951.. | wikipedia | yo |
Oludasilẹ, oludari ati onnko ere naa ni Kenji Kamiyama, o si ṣe àfihàn àwọn onsere ti Chika Umino ṣẹda àti àwọn idaraya ti ilé iṣẹ́ Production I.G.. | wikipedia | yo |
A gbé eré yìí kalẹ̀ lórí ìtàn ti Kamiyama kọ ní ìgbà kan rí, òun sì ní ojúlówó eré àkọ́kọ́ tí ilé iṣẹ́ ẹ̀rọ mohuntúútúúnit Dnemina gbé jáde.Àwọn Ìtọ́kasí== | wikipedia | yo |
A bi Chioma Chukwuka ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kẹta ọdún 1980.. | wikipedia | yo |
A tun n pe orukọ rẹ ni Chioma Chukwuka Akpotha tabi Chioma Akpotha, o jẹ oṣere ati Olùgbékalẹ̀ fiimu ni orilẹ-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2007 o gba ami ẹyẹ ti awọn oṣere tiata fun ilẹ Afrika gẹgẹbi obinrin ti o dara julọ ti o si kopa gegebi osere akoko lobinrin ninu ere ati ami eye fun awon dudududu ni Hollywood gẹgẹbi oṣere lobinrin ti o dara ju lọ.Iṣẹ Awọn Eniyan Alààyèawọn Ọjọ́ìbí ni 1980.. | wikipedia | yo |
Alexander Boris de Pfell Johnson (; Born 19 June 1964) jẹ́ olóṣèlú ara ilé Britẹni tí ó wà nípò àṣẹ alákòóso àgbà ilẹ̀ Britẹni àti aṣíwájú ẹgbẹ́ òṣèlú The Conservative Party Lọ́wọ́lọ́wọ́, lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú ẹgbẹ́ òṣèlú Conservative láti July 2019. Àwọn ará tani | wikipedia | yo |
Theresa Mary May (; Brasier; ibi 1 October 1956) jẹ́ olóṣèlú ará Britani tó fìgbà kan wà nipo gegebíu alákóso agba ilẹ̀ Britani àti olórí ẹgbẹ́ olóṣèlú Konsafeti lati 2016 de 2019.Ìtọ́kasí ara Britani.. | wikipedia | yo |
gẹ̀gẹ̀s Gíwá Polytechnic jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga Gbogbonìṣe tí ó wà ní ìlú Owó ní ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó gbàṣẹ gbòntẹ̀ láti ọwọ́ àwọn Ìgbìmọ̀ tí ó ń rí sí ètò ẹ̀kọ́ Gbogbonìṣe nílẹ̀ Nàìjíríà láti jẹ́ kí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ aládàáni ti ìjọba ìpínlẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àjọ tí ó ń rí sí ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ Gbogbonìṣe ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ( National Boars of Technical Education) àti Institute of Chatered Accountant.. | wikipedia | yo |
.Wọ́n dá ilé-ẹ̀kọ́ yìí sílẹ̀ ní ọdún 1979 pẹ̀lú àṣẹ látẹnu Gómìnà lásìkò ìjọba ológun Sunday Tuyo wípé kí ó ma jẹ́ The Polytechnic Owo.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí ni gómìnà Adékúnlé Ajasin bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣagbátẹrù iké-ẹ̀kọ́ náà ní kété tí ó gorí oyè àṣẹ ní ọdún 1980.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yí orúkọ iké-ẹ̀kọ́ yí padà Ondo State Polytechnic ní ọdún 1990.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí yóo fi tó ọdún 2010, ilé-ẹ̀kọ́ náà ti ní àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó tó ẹgbẹrun mẹrin (4,000).. | wikipedia | yo |
ilé-ẹ̀kọ́ yìí ní àwọn agbọ́nrin ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ lábẹ́ ẹ̀ka Faculty ti Engengen, Science àti Technology, LEMS, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Bakan naa ni wọn n ṣapá ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ nipa, Imọ ẹrọ, Imọ Iwadi Ayika, Imọ iṣiro, Imọ eto ọrọ aje ati isuna.. | wikipedia | yo |
Ilir meta (; Ọjọ́ìbí 24 March 1969) je oloselu ara Albania to ti wa nipo bi Aare ile Albania lati 24 July 2017.Ìtọ́kasí awon Aare ile Albania.. | wikipedia | yo |
Olusese Abiodun Makinde ni a bi ni ojo karundinlogbon osu kejila, odun 1967 (25 December 1967).. | wikipedia | yo |
O je onisowo, oloselu ati Olore àtinúwá omo orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Oun ni Gomina ti o n bẹ lori alefa lọwọlọwọ ni IpinleOyo Oyo ni apa iwo-oorun ile Naijiria.. | wikipedia | yo |
Wọ́n dìbò yàn-án ní ọdún 2019 lábẹ́ àsíá ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party (PDP) ó jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ àti onímọ̀ nípa ìwọ̀n epo àti afẹ́fẹ́ gáàsì (fluid and Gas mẹtẹring).ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ àti Èkóa bí Makinde sí ilé pa Ọlátúbọ̀sún Makinde, àti Abigail Makinde Gami ní àdúgbò Àìdi, Ọjà'bá, ní ìlú Ìbàdàn, ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.. | wikipedia | yo |
Makinde bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ẹ̀kọ́-ìbẹ̀rẹ̀ St Paul Primary School.. | wikipedia | yo |
Ó parí ẹ̀kọ́- ìbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní St Michael Primary School,ní yẹ metu.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásítì ìlú Èkó níbi tó ti gba ìwé-ẹ̀rí Bachelor degree nínú ìmọ̀ ObáAN Engineering.àwọn Ìtọ́kasíàwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo.. | wikipedia | yo |
Gregory Oliver Hines (February 14, 1946 – August 9, 2003) jẹ́ oníjó, òṣèré, akọrin àti onímọ̀ìjọ ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasíàwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Samuel Sochukwu Okwàrà (19 May 1964 – 12 August 1989) jẹ oni-iṣẹ agbabọọlu- to gba bọọlu fun Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ agbẹjọ́rò lórí òfin ìbáṣepọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè láti Pontifical Lateran University ìlú Romu.. | wikipedia | yo |
O ku nigba to wo lulẹ nitori idina inu okan-àyà to ba ni iṣẹju 77k ere boolu Ikópa ninu Ife-eye Agbaye pelu Angola ni papa isere National ni Surulere, Lagos State ni ojo 12 osu kejo odun 1989.Awon agbaboolu-ede ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Minnie Joycelyn elders (àbísọ Minnie Lee Jones; August 13, 1933) jẹ́ is an American oniwosan ọmọdé àti alakoso ètò ilera igboro.. | wikipedia | yo |
O jẹ ọgagun Igbakeji adari ni ile-iṣẹ awon ọmọṣẹ́ alafúnṣẹ́ ise ilera igboro ati omo Afrika Amẹrika akoko to je yiyan sipo gege bi oniwosan agba orile-ede Amerika, o fi ipo yi sile ni 1994.. | wikipedia | yo |
Lọwọlọwọ elders je ojogbon eniowo ninu eko iwosan omode ni Yunifasiti ẹwìrì fun sayensi oniwosan.Ìtọ́kasí oniwosan agba orile-ede Amerika.. | wikipedia | yo |
(tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1960) jẹ́ oníṣòwò àti olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Yorùbá láti ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O jẹ gomina ipinle ogun nigbati o bori idibo ti Gomina ni ọdun 2019 labẹ Aásìya Egbe-Oselu (APC).. | wikipedia | yo |
Dapo Abiodun ni olori Igbimọ ti Corporate Affairs Commission.. | wikipedia | yo |
O tun jẹ alakoso ati oludari ti ile epo heyden ati oludasile first power Limited.. | wikipedia | yo |
Ni ojo kewa osu keta odun 2019, igbinmo ti o n dari idibo ni ile Naijiria eyi ti o je Independent Electoral Commission kede Dapo Abiodun gege bi Gomina ti a dibo yan ni Ipinle Ogun.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣe ìbúra fún un gẹ́gẹ́ bí gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn ní ọjọ́ KonỌlọ́pàá, oṣù karùn-ún, ọdún 2019 (29 May 2019)ìgbà Ewedàpọ̀ Abiodun wà láti odomọ rẹ́mọ ní ìpínlẹ̀ Ògùn.. | wikipedia | yo |
A bi sinu ebi Dokita Emmanuel ati Arabinrin Victoria Abiodun ti won wa lati ranti Remo ni Ila-ọrun Ipinle Ogun ni ojo kokandinlogbon osu karun odun 1960 (29 May 1960).Ẹkọ Abiodun ko eko nipa imo ero ni ile eko giga Fasiti Obafemi Awolowo ti o wa iranse Dapo Abiodun ni alakoso ati oludari ile ise heyden Petroleum (up (Ul), Ile ti epo ti epo ni ile Naijiria.. Ile Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ First Power Limited.ÒDÀDapo Abiodun jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ tí ó dá ẹgbẹ́ alárùdà (Peoples Democratic Party) sílẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, bíbíá ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ onigbale (All Progressive Congress) Lọ́wọ́lọ́wọ́ Bayi nígbàtí Ó fi ẹgbẹ́ tí ó wá tẹ́lẹ̀ sílẹ̀ lẹ́hìn lẹ́hìn gbogboogbo ti ọdún 2015.. | wikipedia | yo |
Ó díje du ipò láti lọ sí ilé Ìgbìmọ̀ asòfin àgbà láti lọ sójú ìla òòrùn ti Ìpínlẹ̀ Ògùn lábẹ́ ẹgbẹ́ onigbale (All Progressive Congress) nínú ìdìbò gbogboogbo tí ó wáyé ní Nàìjíríà ní ọdún 2015 èyí tí ó pàdánù rẹ̀ fún ọmọ ẹgbẹ́ alárùdà (Peoples Democratic Party).. | wikipedia | yo |
Wọ́n yan Dapo Abiodun gege bi okan lara awon asofin agba ti ijoba apapo ile Naijiria ni odun 1988 labe egbe United Nigeria Congress Party (UNCP) eyi ti o ti koya si ile.. | wikipedia | yo |
Ó ti ṣiṣẹ́ sin lábẹ ìgbìmọ̀ Ààrẹ àti ilé isẹ́ lórílórí.Ní ọdún 2019, ó díje nínú ìdìbò tí Gómìnà ní Ìpínlẹ̀ Ògùn lábẹ́ ẹgbẹ́ onigbale (All Progressive Congress).. | wikipedia | yo |
O jẹ ọmọ lẹhin Kristi tòótọ́ ti o si nJỌsìn pẹlu ile ijosin (Mountain of Fire and Loloary Ministry).. | wikipedia | yo |
O ti jẹri pe pẹlu gbogbo bi atako lati ma le de osisi ti Gomina Ipinle Ogun se po to, Ọlọrun si tun mu o un de ibẹ̀.igbesi aye ara rẹAbiodun se igbeyawo si Bámidélé Abiodun lodun 1990, o si bi omo marun-un, lara re ni Oloogbe olugbenga Abiodun, DJ Naijiria kan ti a tun mọ si DJ Olu.Awon itọkasi awon Gomina Ipinle Ogun.. | wikipedia | yo |
Bolaji Abdullahi (A bí ní ọdún 1969) jẹ́ olóṣèlú àti oǹkọ̀wé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà láti Ìpínlẹ̀ Kwara.. | wikipedia | yo |
O wa ninu igbinmo ti Alakoso orile-ede Naijiria tẹlẹ, labẹ akoso Goodluck Jonathan gege bi Minisita fun Idagbasoke ọdọ ni Oṣu Keje ọdun 2011 ati lẹhinna bi Minisita idaraya.ibẹrẹ Aye ati Eko Abdullahi kọ ẹkọ gboye lori ibaraẹnisọrọ lati ile ẹkọ giga Yunifasiti Eko.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2001, pẹ̀lú sikolashipu Chevening, Abdullahi fi orúkọ sílẹ̀ fún ikẹkọ ní ilé ẹ̀kọ́ fún iwadi Ìsókè (Institute of Development Studies) ní Yunifásítì ti Sussex níbití ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ gboyè gíga tí ó peregedé lórí ìṣèjọba àti Ìdàgbàsókè (Governance and Developmentiṣẹ́ Ayanse ní ọdún 1997, Abdullahi darapọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ ìwé ìròhìn tí This Day gẹ́gẹ́ bi oníròrò ṣùgbọ́n lẹ́hìn ọdún kan, ó kúrò láti lọ darapọ̀ mọ́ Apejọ Alábí Afrika (African Leadership Forum).. | wikipedia | yo |
Ó padà ní ọdún 2002 tí ó sì ní ìgaga sí ipò igbákejì olóòtú ti ìwé ìròhìn ní ọdún 2003.. | wikipedia | yo |
Lehinna, wọ́n kọ́kọ́ yan Abdullahi gẹ́gẹ́ bí olùránlọ́wọ pàtàkì fún ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti ipin Gkásókè Assistant Communication and strategy) sí Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara tẹ́lẹ̀, Bukola Saraki ní ọdún 2003 lẹhinna ni ó wá di oludamọran pataki lori imulo àti ipin yíká (Special adviser on Policy and strategy) ní ọdún 2005.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yan Bolaji Abdullahi gẹ́gẹ́ bi koomisoanna fún ètò ẹ̀kọ́ àti ìmọ̀ ẹ̀rọ ti Ìpínlẹ̀ Kwara láti ọdún 2007 sí ọdún 2011.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ síwájú láti lọ sin nínú ìgbìmọ̀ Mínísítà tí Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, Goodluck Jonathan nígbàtí wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bi Mínísítà fún ìsókè ọ̀rọ̀ àwọn ọ̀dọ́ ní Oṣù Keje ọdún 2011.. | wikipedia | yo |
Lehinna ni wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bi Mínísítà fún eré ìdárayá.Ní Oṣù kejìlá ọdún 2016, wọ́n kéde Abdullahi gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé gbogboogbo ti orílẹ̀ (National Bblicity secretary) fún ẹgbẹ́ onigbale (All Progressive Congress).. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kini Oṣù Kẹjọ ọdún 2018, Abdullahi finú fẹ́dọ̀ fí ìwé sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí akọ̀wé gbogboogbo tí ẹgbẹ́ onigbale (All Progressive Congress) tí ó sì kúrò nínú ẹgbẹ́ na.àwọn Ìtọ́kasí 1.. | wikipedia | yo |
Mudashiru Àjàyí Ọbasá jẹ́ agbẹjọ́rò, olóṣèlú ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress ilẹ̀ Nàìjíríà kan.. | wikipedia | yo |
Òun tún ni ó jẹ́ agbẹnusọ fún ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Èkó lọ́wọ́lọ́wọ́.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ á bí i ní ìlú Agege, ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní apá Gúsù ìwọ Ọlọ́run ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ St Thomas Acquinas ní Sùúrù-lérè, ṣáájú kí ó tó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama Archbishop Agy Memorial, ní ìlú Ẹja, ní agbègbè Ìlà-Maja, ní Ìpínlẹ̀ Èkó nibi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gba ìwé ẹ̀rí ìdánwò àpapọ̀ ìwọ̀ oòrùn Ilẹ̀ Adúláwọ̀ (WA).. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 2006.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olóṣèlú ní ọdún 1999, Mudashiru díje dupò sí ipò àga ìjọba ìbílẹ̀ Agege lábẹ́ egbẹ́ òṣèlú Alliance for Democracy bori ó sì borí, léyìí tí ó ṣiṣẹ́ nibẹ̀ láàrín ọdún 1999 sí 2002.. | wikipedia | yo |
Ewe, o ran dije dupo si ile Igbimọ Aṣojusofin Ipinle Eko ni ẹkun ijọba ibilẹ Agege ni ọdun 2019, ti o si tun jawe olubori ninu idibo naa, ti o si so di agbenuso fun ile igbimo naa ni Ipinle Eko.Awon itọkasi awon Ọjọ́ìbí ni 1972awon agbejoro ara Naijiriaàwọn eniyan alààyè.. | wikipedia | yo |
Gbenga Adeboye (1959 -Oṣù Kẹrin 2003) jẹ́ akọrin, Veneriin, Olóke ètò orí rédíò àti Olùdarí ayẹyẹ.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀Elijah Olúwagbemiga Adeboye ni wọ́n bí ní ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù Kétata ọdún 1959 (30,9] ní ìlú Ọdẹ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Osun, ní Gúsù ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríàgbo-gbodò iṣẹ́ rẹ̀ ó jẹ́ Gíntarún sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ Orí Rédíò ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 1980, ní bi tí ó ti gba ìnagijẹ rẹ̀ “Fún Odulo Oduọ́lọ́jì | wikipedia | yo |
gbajúgbajà òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ìdòwú Philip ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sí “Ìyá Rainbow” ṣàpèjúwe Gbenga gẹ́gẹ́ bí Adérì-pọ̀ àti aláwàdà tí ó ma ń tọrẹ àtinúwá fẹ́ni tó bá ní lo ìrànlọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó ń sọ bí Gbenga ṣe fún òun ní ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ àkọ́kọ́ tí òun kọ́kọ́ ní láyé òun.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tu ṣàpèjúwe olóògbé náà gẹ́gẹ́ bí ontàjà àti aláfihàn fàbú lọ́nà ìbílẹ̀ ṣáájú kí ó tó kú látàrí àìsàn tí ó nírú pẹ̀lú kídìnrín, ní ọjọ́ kẹẹdọ́gbọ̀n oṣù kẹrin, ọdún 2003.Ẹ tún lè wo wọ́ Yinka Ayefele - ṣe ìgbóríyìn fún Adeboye.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ọjọ́aláìsí ní 2003àwọn Ọjọ́ìbí ní 1959.. | wikipedia | yo |
Olaṣúpó Shasore, Agbẹjọro Agba ni orile-ede Naijiria (ojo ibi - ojo keji-le-logun osu kini odun 1964) je onimo nipa ofin.. | wikipedia | yo |
O jẹ ọkan lara awon oludasile ati alabaṣepọ ninu ile-iṣẹ ofin ti Alp (Ofin Ilu Afirika).. | wikipedia | yo |
O jẹ Agbẹjọro Agba ati alabojuto Ẹka Ìdájọ́ ti Ipinle Eko lati ọdun 2007 titi ọdun 2011.. | wikipedia | yo |
Shasore jẹ́ Agbẹjọ́rò agba~a ti Nigeria (SAN) ati okan gboogi ninu egbe awon Alagbawi ni orile ede Naijiria.. | wikipedia | yo |