cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
A sọ ní Pakistan àti Indian-tí a nṣe KaSHsh àti pé èdè èdè ti orílẹ̀-èdè náà ní.. | wikipedia | yo |
A sọ ni gbogbo India, paapa ni àwọn ipinlẹ Andhra Pradesh, Delhi, Bihar àti Uttar Pradesh... | wikipedia | yo |
Dassa-Zoume, tun mọ si Igbo Ixsha tabi Dassa, Ilu ni Ilu Benin, lori ọna oju irin irin ajo Cotonou -to- Parakou ati akoko ọna opopona ariwa-guusu.. | wikipedia | yo |
Ilu naa ni wiwa agbegbe ti , ati pe ti 2013 ni iye eniyan ti 112,118.. | wikipedia | yo |
Ita ẹgbẹ jẹ abule kan ti o wa ni ijoba ibile ti ipokia ti Ipinle Ogun, a mọ on nipasẹ awọn iṣẹ-ogbin ti o tobi julọ ni ayika agbegbe ati nipa jijẹ ọkan ninu awọn ti o tobi julọ ti ọpẹ ni Ipinle Ijọba ti Ogun.Koodu ifiweranṣẹ Itajo ifiweranṣẹ ita ni 11110gbọ́dọ̀ Iṣẹeko itọkasi ẹgbẹìlú to wa labẹ ijọba ibilẹ ipoki ati Ungiga translations.. | wikipedia | yo |
Sunpe Rachamámà jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Táílá.Àwọn akọrin ará Thalá.. | wikipedia | yo |
Kim Da-hyun jẹ olorin ọmọ Orílẹ̀-èdè Gúsù Korea.Àwọn akọrin ará Korea gúúsù.. | wikipedia | yo |
Fásitì Odùduwà jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ àdáni tí wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 2009.. | wikipedia | yo |
Àwọn olùgbé Ilé-Ifẹ̀ tó iye bí ẹgbẹ̀rún lọ́nà áàdọdò, ọgọ́rùún méjì ólé mọ́kàndínláàdọ́ta àti àti mọ́kàndíneEUún ènìyàn (50,000-249,ìdájọ́).. | wikipedia | yo |
Àjọ (NUC) tí ó ń rí sí ìgbòkè-gbodò ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì nílé Nàìjíríà fòntẹ̀ má báṣẹ́ rẹ̀ lọ òlú ẹ̀rí tó yánárántí tí wọ́n sì to ilé-ẹ̀kọ́ náà sí ipò kẹrìntẹ́júrùún (104) láàrín àwọn ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ikẹ̀ Nàìjíríà, nígbà tí ó wà ní ipò ẹgbẹ̀rún kan ólé ọgọ́rùn mẹ́fà àti mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n (10617) ní àwùjọ Ilé-ẹ̀kọ́ Àgbáyé.. | wikipedia | yo |
fáfitì Odùduwà ń kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn ní ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ jákè-jádò àgbọ́ọ́n-gbé ìmọ̀ Loíkiní.Odùduwà.. | wikipedia | yo |
Fásitì Odùduwà fìdí kalẹ̀ sí ìlú Ipetumodu, Ilé-Ifẹ̀, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.. | wikipedia | yo |
Ọmọba Rahmon Adégòkè Adédoyin ẹni tí wọ́n bí ní ọjọ́ kíní osù kíní, Ọdún 1957 (born January 1, 1957) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè is a Nàrírs | wikipedia | yo |
Olùkọ́ni, àti bajú-gbajà oníṣòwò ,bákan náà ni ó jẹ́ olùdásílẹ̀ iké-ẹ̀kọ́ Fásitì Odùduwà àti ilé-ẹ̀kọ́ gbogb-níṣẹ́ Polytechnic, ní Ilé-Ifẹ̀ nínú ìtàkúṣọ rẹ̀ pẹ̀lú aṣojú ilé-iṣẹ́ ìwé ìròyìn Vanguard, Rahmon fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé Ọba Okùnadé ṣíjúadé tí ó wàjà kọjá nílé-Ifẹ̀ ni ó yan ọgàá gẹ́gẹ́ bí Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ Ṣáájú kí ó tó gbésẹ̀ nítorí iṣẹ́ ìdàgbà-sókè ribiribi tí òun gbé ṣe ní ìlú náà, pàápàá jùlọ nílẹ̀ Yorùbá lápapọ̀.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé, Èkó àti iṣẹ́ rẹ̀ Rahmon Adélà ni wọ́n bí ní ẹní Àakui, ní Ilé-Ifẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Ọ̀ṣun níbi tí ó ti parí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ilé-ẹ̀kọ́ girama rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ó tẹ̀ síwájú nílé-ẹ̀kọ́ Fásítì Ọbafẹ́mi Awólọ́wọ̀ níbi tí ó ti gba oyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ní ọdún 1983, lẹ́yìn èyí ni ó tú kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìṣirò ( mathematics Education).. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ fásitì Centurion International ní orílẹ̀-èdè California, níbi tí ó ti gba oyè ìmọ̀ ẹlẹ́kẹẹ̀sán (master's degree), tí ó sì tún gba oyè ìmọ̀ ọ̀mọ̀wé ( doctorate degree) nílé ẹ̀kọ́ All Saints University School of Medicine, New York City, ní ọdún 1966.Pẹ̀lú ìgbìyànjú rẹ̀ láti gbé ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ sókè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó dá ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ( Polytechnic), Ilé-Ifẹ̀ kalẹ̀ ní ọdún 1984 tí ó sì dá fásitì Odùduwà náà kalẹ̀ ní ọdún 2009.. | wikipedia | yo |
Rahmon jẹ́ ọ̀kan gbòógì lára àwọn InduIndukú Statistikir ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríààwọn ìtọ́ka sí àwọn oníṣòwò ará Nàìjíríààwọn Ọjọ́ìbí ni 1957àwọn ènìyàn Aàyé.. | wikipedia | yo |
Gabriel Mojísọ́lá Babátúndé ní wọ́ bí ní ọjọ́ Kẹrìnlá oṣù Kẹ́sà, ọdún 1938 (September 14, 1938) ní ìlú Akinmorin, ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀Afijio Local Government Area of in Ìpínlẹ̀ Òndó Nigeria.. | wikipedia | yo |
Òun ni ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ fún ìmọ̀ Sáyẹ́nsì nípa ẹranko (Professor of Animal Science) ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ Babátúndé lọ ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní St.. | wikipedia | yo |
John School, ní Akinmorin láàrín ọdún 1944-1950, tí ó sì tún lọ síí Èkó St.. | wikipedia | yo |
David School, ní ìlú Kuku ní Ibadan, laarin ọdun 1951-1952.. | wikipedia | yo |
ó tẹ̀ síwájú nílé-ẹ̀kọ́ Government College tí ó wà ní ìlú Ìbàdàn láàrín ọdún 1952-1959.. | wikipedia | yo |
Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè àkọ́kọ́ ( B.Sc (hons) nínú ìmọ̀ ọ̀gbìn, tí ó sì jáde pẹ̀lú ìpele Kejì (Second Class Upper Division) ní ìlú London, ó gba oyè ìmọ̀ ẹlẹ́kejì ìyẹn (M.Sc), àti oyè Ọ̀mọ̀wé (PhD) nínú ìmọ̀ (Animal Nutrition, monoogacs) ní Fásitì Cornell , ní ìlú Ithaca, New York ní ọdún 1967.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni ó tún ní àwọn ìjànján ìwé ẹ̀rí (postgraduate and diplomas and qualification, as an fáEA trainée) lórí bí a ṣe ń lọ (Radioisotopes àti radiation) nínú ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Ẹranko(Animal Science and Vetedàrùn Medicine) láti ilé-ẹ̀kọ́ Belgrade, Yugoslavia ní ọdún 1970.Àjọ àti ìjọ̀mọ ẹgbẹ́ rẹ̀ Babátúndé jẹ́ ọ̀kan lára àwọn American Registry of Professional Animal Scientists (ARpas) láti ọdún 1974.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Nigerian Society for Animal Production.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, ó tún jẹ́ American Society of Animal Science.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni ó tún jẹ́ ọ̀kan lára àjọ Agricultural Society of Nigerian, tí ó sì túnnjẹ́ ọ̀kan lára àjọ Science Association of Nigeria and Nigerian Institute of Animal Science.Ìyànìyàn rẹ̀ Ọ̀jọ̀gbọ́n Babátúndé ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ Onípò Kejì(Lecture II) ní ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ Animal Science Department, Fásitì Ìbàdàn láàrín ọdún 1967-1969.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sọọ́ di olùkọ́ onípò kíní (Lecturer i) ní ẹ̀ka ètò kan náà, tí ó sì ṣiṣẹ́ nípò yí fún ọdún kan kí ó tún tó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Ọ̀jọ̀gbọ́n ní abala iètò ẹ̀kọ́ Animal Nutrition nínú ọgbà kan náà láàrín ọdún 1972-1977.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàn án sípò Ọ̀jọ̀gbọ́n Animal Nutrition (Monogastrics) ní abala ètò ẹ̀kọ́ Animal Science kan náà ní Fásitì Ìbàdàn fún sáà ètò-ẹ̀kọ́ 1976/77 .. | wikipedia | yo |
Oun naa tun ni olóòtú agba fún àjọ oníwèé ìròyìn nípa ipese eranko (Animal Production) láàrin ọdún 1977-1980.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, ó tún jẹ́ ọ̀gá àgbà fún abala ẹ̀ka ẹ̀kọ́ Animal Science ní Fásitì Ìbàdàn.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni ó run jẹ́ alákòóso fún ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nípa ohun ọ̀gbìn àti ìdákò (Dean, Faculty of Agriculture and forstry) ní ọdún 1980 sí-1982.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ Rector àkọ́kọ́ fún ilé-ẹ̀kọ́ College of Agriculture and Natural Resources, Bendel State tí ó ti di (Edo State) báyìí láàrín ọdún 1982-1984.. | wikipedia | yo |
Lákòótán , òun ni Gíwá àgbà àkọ́kọ́ (first Dean and gbogbo Vice-Chancellor) fún ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì Agriculture,Abeokuta.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1938.. | wikipedia | yo |
Toyin Abraham tàbí Olutoyin Aimakhu; ni wọ́n bí ní (September 5, 1984).. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ òṣèré orí ìtàgé , olùgbéré-jáde àti adarí eré, Ọmọ rilẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bi ní ìlú Auchi, tí ó jẹẹ́ ìlú kan ní town in ìpínlẹ̀ Ẹdó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Amo sa, o bere aye re ni iluIbadan, ti o je olu ilu ipinleOyoni iwo oorun ile Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó gba ìwé ẹ̀rí HND (Higher National Diploma) ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ìlú Ìbàdàn ìyẹn (Ibadan Polytechnic), lásìkọ́ yí, ó jẹ́ akẹgbẹ́ pẹ̀lú Dibie, C.B.N aka X7, Tóyìn Abraham ti fara hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, tí ó sì tún ṣẹ̀ṣẹ̀ kópa nínú sinimá àgbéléwò aré tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Black Val.Iṣẹ́ rẹ̀ Tóyìn bẹ̀rẹ̀ eré orí ìtàgé rẹ̀ nígbà tí gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bukky Wright, wá sí ìlú Ìbàdàn láti yàwòrán eré kan .Ó ti darí, kópa àti gbé eré jáde fúnra rẹ̀, lára rẹ̀ ní Àlàní Bàbá Làbákẹ́ àti d Èmi ni.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí òṣèré amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ obìnrin tó dára jùlọ (Best Supporting Actress) nínú eré orí ìtàgé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ "Ẹ̀bi mi ni" Nínú àmì ẹ̀yẹ 2013 Best of Nollywood Awards , bákan náà ni wọ́n yan Jọkẹ́ Múyìwá fún Best Lead Actress nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Ayítakẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, ọ̀pọ̀ àwọn olóṣèlú ló ti pèé láti bá wọn polongo ètò ìdìbò fún Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ̀lẹ̀ tí ó jẹ́ adíje dupò sí orí àpèrè Ààrẹ ìyẹn Goodluck Ebele Jonathan ní ọdún 2015.. | wikipedia | yo |
Tóyìn pàá pàá sọ wípé òún lè kú torí ẹgbẹ́ òṣèlú People Democratic Party (PDP) kú tí ó jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú tí adíje dupò náà ti ń díje.. | wikipedia | yo |
naruMáki (1960– ilẹ̀ Japan lọwọlọwọ, ohun ni ọba 126th gẹ́gẹ́ bí àṣà ifọbàjẹ́ Japan.Ìtọ́kasí awọn Ọbalúaye Japan.. | wikipedia | yo |
Prince Rogers Nelson (ojo 7 osu kefa, 1958 - ojo 21 osu kerin, 2016) je akorin, oludasile orin, olorin, olootu awo-orin, osere, ati oludari fíú ara Amerika.. | wikipedia | yo |
Pẹlu iṣẹ́ kan ti ó wà ni àwọn ọdún mẹrin, ọmọ-ọ̀dọ̀ ni a mọ̀ fún iṣẹ́-ṣíṣe tí ó ní ìmọ̀ràn, ipò iṣan flamboyant, ìgbádùn oriṣiriṣi aṣa ati lilo ti atíkè, ati ibití ó gbọ̀ọ̀rọ̀.. | wikipedia | yo |
Oniruru-oludasi-ọrọ̀, a kà ọ pe o jẹ aṣeyọri gìG kan ati pe o tun ni oye ni ti ndun awọn ilu, ariyanjiyan, bass, awọn bọtini itẹku, ati Olùpasilẹ.. | wikipedia | yo |
Prince ṣe igbimọ ni Minneapolis, eyiti o jẹ ipilẹ ti apata funkki pẹlu awọn eroja ti Syth-pop ati igbiyanju tuntun, ni opin ọdun 1970.Awọn itọkasiawọn orisun awọn ẹlẹ́bùn Grammyawọn akọrin ara Ameria akọrin Funk ara Ameria Ojoalaisi ni 2016awon Ọjọ́ìbí ni 1958articles with Hcardṣàwọn ọmọ Afrika Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ọmọba Olayiwola Fatai Olagun, ti gbogbo ènìyàn mo si Fatai Rolling Dollar ni wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù keje, ọdún 1927(22 July 1927) tí ó sì daláìsí ní ọjọ́ Kejìlá oṣùKèfà , ọdún 3013 –12 June 2013), ni ó jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní otá-èdè Nàìjíríà, ní ó jẹ́ olórin Highlife, àti Jùjú.. | wikipedia | yo |
Ó kù ní dédé ọmọ ọdún mẹ́fàdélẹ̀ (86), Aláṣẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Goodluck Jonathan sì ṣáṣápọ́nlé rẹ̀.Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin rẹ̀ ní ọdún 1953, ó sì ti kọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ olórin níṣẹ́ orin.. | wikipedia | yo |
Lára wọn ni Olóyè Ebenezer Obey àti Okoye Orlando Owoh tó ti dolóògbé.. | wikipedia | yo |
Fatai di ìlú mọ̀ọ́ká pẹ̀lú ìṣọwọ́ ta jìtá rẹ̀ lọ́nà ara.. | wikipedia | yo |
Lára àwọn orin aládùn rẹ̀ ni "Wọ́n kéré sí Si Number Wa".Ó dá ẹgbẹ́ akọrin tirẹ̀ sílẹ̀ ní ọdún 1957 tí ó pè ní Fatai Rolling Dollar and his African Rhythm band, lábẹ́ ilé iṣẹ́ Phillips West Africa Records.Ikú rẹ̀ ó kú nígbà tí ó ń sùn lọ́wọ́ ní ilé rẹ̀ tí ó wà ní ìlú Ikorodu, ní Ìpínlẹ̀ Èkó ó sì jẹ́ ẹni tí ẹ̀mí rẹ̀ gùn jù nínú àwọn olórin ilẹ̀ Nàìjíríà jùlọ.Àwọn ìtọ́kasí àwọn ọjọ́aláìsí ní 2013àwọn Ọjọ́ìbí ní 1927.. | wikipedia | yo |
Ìyìnbọn mọ́ ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ṣọ́ọ̀sì ní Charleston (tí a tún mọ bí ìfkúparun ṣọ́ọ̀sì ní Charleston) jẹ́ ìṣẹ́lẹ̀ ìfìbọn pa ọ̀pọ̀ ènìyàn tó ṣẹlẹ̀ nígbàtí Dylann Roof, tó jẹ́ oníṣègbéraga àwọn aláwọ̀funfun ọmọ ọdún 21 fìbọn pa àwọn aláwọ̀dúdú ará Amẹ́ríkà mẹ́sàn (ti olùṣọ́-àgùtàn àgbà àti, alàgbà ilé aṣòfin Clementa C.. | wikipedia | yo |
Pinckney wa ninu wọn) nígbà tí wọ́n únṣe ìsìn adura ninu Ṣọ́ọ̀ṣì Emanuel African Methodist Episcopal ní Ìlú Charleston, South Carolina, ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ 17 Oṣù kẹrin, ọdún 2015.. | wikipedia | yo |
Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì tó ṣe iṣẹ́ ibi rẹ̀ tán, àwọn ọlọ́ọ̀pá gbá Roof mú ní Shelby, North Carolina.. | wikipedia | yo |
Roof jẹ́wọ́ iṣẹ́ ibi tó ṣe nírètí pé yíò fa ogun elẹ́yàmẹyà wá.. | wikipedia | yo |
Ṣọ́ọ̀ṣì ti Roof ti lọ pa àwọn ènìyàn ló jẹ́ ìkan núnú àwọn ṣọ́ọ̀ṣì aláwọ̀dúdú tó dàgbàjùlọ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, tó jẹ́ ibùdó fún àgbájọ àwùjọ nípa àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú.. | wikipedia | yo |
Wọ́n pinu pé Roof le dúró fún ìgbẹ́jọ́ ní ilé-ẹjọ́ ìjọba àpapọ̀, ní oṣù Kejìlá ọdún 2016 wọ́n dá Roof lẹ́bi ẹ̀sùn 33 tí wọ́n jẹ́ ọ̀ràn ìkórira lábẹ́ ìjọba àpapọ̀ àti ẹ̀sùn ìpànìyàn tó ṣe pẹ̀lú ìyìnbọ́n náà.. | wikipedia | yo |
Ní Ọjọ́ 10 Oṣù Kínní, ọdún 2017, wọ́n dá ẹjọ́ iku fun.. | wikipedia | yo |
lọ́tọ̀ Roof ní ẹ̀sùn ọ̀ràn ìpànìyàn mẹsan ní ilé-ẹjọ́ ìpínlẹ̀ South Carolina.. | wikipedia | yo |
Ní Oṣù Kẹrin ọdún 2017, Roof gbà pé òhun jẹ̀bi ẹ̀sùn mẹ́sẹ̀ẹ̀sán tí ìjọba ìpínlẹ̀ fi kan kó le baà yẹra fún ìdájọ́ ikú kejì, nítoríẹ̀ wọ́n dá ẹjọ́ Ìjùwọ́n ayérayé fún, fún ìkọ̀ọ̀kan àwọn ẹ̀sùn náà, èyí sínà fún ìjọba àpapọ̀ láti pàṣẹ ikú rẹ̀ nígbà tó bá ya.Roof fìgbàgbọ́ rẹ̀ hàn nípa ìkórira elẹ́yàmẹyà nínú Manifesto tó kọ sórí Internet kó tó lọ yìnbọn pa àwọn ènìyàn lọ́jọ́ náà, àti nínú ìwé-ìṣẹ̀lẹ̀ tó kọ ní túbú lẹ́yìn náà.. | wikipedia | yo |
Elé ṣáájú kí ìbọn náà, àti àkọsílẹ̀ kan tí a kọ láti ilẹ̀-ẹ̀hìn lẹ́hìnnã.. | wikipedia | yo |
Awọn aworan ti a fi sori aaye ayelujara fihan Ọṣọ ti o nmu pẹlu awọn ami-ami ti o ni nkan ṣe pẹlu itẹsiwaju funfun ati pẹlu awọn fọto ti Flag of Confederate.. | wikipedia | yo |
Ìbọn yiyan ni ijiroro lori ifarahan onibara rẹ, ati tẹle awọn ibon yiyan, South Carolina Gbogbogbo Apejọ dibo lati yọ awọn Flag lati Ipinle Capitol ilẹ.Awon to fikú da lòrò awọn to fikú da lòrò je mẹsan, obinrin mefa ati Okujrin meta ti gbogbo won je omo Afrika Amẹrika ijo Methodist.. | wikipedia | yo |
Awon mejo ku lesekese nibe; eni kesan, Daniel Simmons, Ku ni Musc Medical Centre.. | wikipedia | yo |
gbogbo wọn kú pa nípasẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìbọn Gunmo ti fìkán ní súnmọ́ ibití ó.. | wikipedia | yo |
Àwọn ènìyàn márùn tí ó yẹ ní ìhámọ́ tí kò ní agbára, pẹ̀lú Felicia Sanders, ìyá tí ó ti pa láìṣẹ̀ TYwanza Sanders, àti ọmọ-ọmọ ọmọ rẹ̀ márun ọdún, pẹ̀lú Polly Sheppard, ọmọ ẹgbẹ́ ẹ̀kọ́ Bíbélì kan.. | wikipedia | yo |
Aya iyawo Pinckney ati awọn ọmọbirin meji tun wa ninu ile lakoko ti ibon.. | wikipedia | yo |
Pinckney (41) - wòólì àti alàgbà ilé-aṣòfin South Carolina. | wikipedia | yo |
Cynthia Marie Graham 1461 (54) - Bible Study member and Dáwe for the Charleston County Public Library System; Sister of Politi and former state Senator Malcolm Graham. | wikipedia | yo |
Susie Jackson (87) - a Bible Study and Church Choir member.. | wikipedia | yo |
DePayne Middleton-Doctor (49) - a Pastor who was also employed as a school administrator and AdLuther Cooratorator at Southern Welẹ̀s University. | wikipedia | yo |
TYwanza Sanders (26) - a Bible study member; Granìràwọ̀phew of kẹ́as Susie Jackson.. | wikipedia | yo |
Simmons (74) - A Pastor Who also served at greater Zion ame Church in Awẹ́ńdáw. | wikipedia | yo |
Sharonda Coleman-sing (45) - a Pastor; also a speech therapistpist and track coach at Goose Creek high school; mother of LL proọ̀rá Chris singleton. | wikipedia | yo |
Myra Thompson (59) - a Bible study teacher.itọkasi.. | wikipedia | yo |
Cartagena jẹ́ ìlú ní KoloÌDÁ àti oluilu apá Bolivar Department... | wikipedia | yo |
Cour nationale du droit d'asile(eyiti o jẹ igbimọ ti awọn igbasilẹ ti awọn aṣoju ) jẹ ile-ẹjọ ti Faranse ti o ṣeto lati ṣe ayẹwo awọn ẹjaduro lati ipinnu ti OFPRA, fifun, kiko tabi yọkuro ipo asasala (wo ẹtọ ti ibi aabo ) ati aabo .. | wikipedia | yo |
O wa ni 35, rue Cuvier 93558 Montreuil, Seine-Saint-Denis ni ilu Faranse.. | wikipedia | yo |
Ile-iṣẹ Gropé D'Information et de Soutien des imterres ) jẹ agbari-ọrọ ti ko ni èrè ti France fun awọn ẹtọ ẹda eniyan ti a da ni ọdun 1972 lati dabobo ẹtọ awọn ofin ati ẹtọ ẹtọ ti awọn ajeji ati awọn aṣikiri ati lati nija fun ominira iyipo ni awọn aala.. | wikipedia | yo |
O pese alaye ati atilẹyin fun awọn aṣikiri nipasẹ imọ rẹ ti ofin Iṣilọ, Faranse, European ati, ni awọn ọna kan, Ilu okeere, ati iriri ti awọn iṣe Iṣilọ.. | wikipedia | yo |
O dabobo awọn ajeji, nfunni ni ikẹkọ ati awọn iwe-aṣẹ ati ki o ṣe alabapin ninu ariyanjiyan lori awọn imulo Migration.awọn ita ita ile-iṣẹpages with unreviewed translations.. | wikipedia | yo |
Awọn Association fun imudani awọn ẹtọ ti awọn ibanikapo fun walk okunrin ati awọn okunrin to o do obinrin, Iṣilọ ati ibugbe (Ardhis) jẹ kan French ti kii-ere jo, mo ti anfani gbogboogbo, ti idi ni, ni ọkan owo, awọn irọ orin ti LGBTI + ajeji tabi awọn alabaṣepọ Franko-ajeji ninu igbiyanju wọn lati ni ẹtọ ti ibugbe wọn mọ ni Faranse, ati, keji, igbasilẹ ti LGBTI ti awọn ajeji + eniyan ti o fẹ lati beere fun ibi aabo ni France.. | wikipedia | yo |
Ti a ṣẹda ni ọdun 1998, Ardhis jẹ ọmọ ẹgbẹ ti LGBT Ile-iṣẹ Paris-Ile-de-France, ati Pẹlupẹlu Faranse fun ibi aabo (CFDA)... | wikipedia | yo |
Débọ̀ Ògúndoyin jẹ́ olólúlúlú ọmọ orílẹ̀ èdè [[Nàìjíríà]] [[Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òun ni ó jẹ́ aṣojú ẹkùn Èrúwà ní ìlà Oòrùn ìjọba ìbílẹ̀ Ìbàrà àti agbọ̀rọ̀sọ tàbí agbẹnusọ fún ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ẹlẹ́kẹẹ̀sán irú rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ làbẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP).. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí Débọ̀ ní ọjọ́ Kejìdínlógún oṣù Kejì ọdún 1988 (18 02, 1988), òun ni ó jẹ́ aṣòfin àti agbẹnusọ́ fún ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí ó jẹ́ ọ̀dọ́ nínú ìtàn iké ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.. | wikipedia | yo |
O de enu ise ni ojo kewa osu karùnún odun 2019 (June 10, 2019).Ìgbé-ayé ati eko re Débọ̀ wa lati Èrúwà ti o je ilu kan ni agbegbe ijoba ibile ila oorun barapa ni Ipinle Oyo.. | wikipedia | yo |
O lọ si ile eko fasiti Babcock .ẹbí rẹ Débọ̀ Ògúndoyin jẹ ọkan lara awọn ọmọ Oloye Adeṣeun Ògúndoyin ti o jẹ ti o jẹ oniṣowo pataki ati olójú àánú pẹlu ọlọ́rẹ àtinú wa.. | wikipedia | yo |
Débọ̀ pàdánù baba rẹ̀ nígbà tí ó wà ní èwe ní ọdún 1991.. | wikipedia | yo |
ChanyẹOl jẹ olórin ọmọ orilẹ-ede Korea guusu.Àwọn akọrin ara Korea gúúsù.. | wikipedia | yo |
PornẸ̀ṣẹ̀ Songsaeng (1960-2021) jẹ́ gbajúmọ̀ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Tláǹdì.Àwọn akọrin ara Thalá.. | wikipedia | yo |
Fọn thanaṣọttron jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Thaláǹdì.Àwọn akọrin ará Thalá.. | wikipedia | yo |
Wọlé ọjọ́ ni wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹfà, ọdún 19884.(Bí 6 Okudu 1984).. | wikipedia | yo |
O dìlù mọ̀ọ́ká ní inú iṣẹ́ sinimá nílẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 2009, lẹ́yìn tí ó gbé ipò kẹ́rin nínú ìdíje Amstel Malta Box Office.Ẹ̀kọ́ rẹ̀ o gba oyè ìmọ̀ ẹ̀kọ́ nínú iṣẹ́ àtinúdá (Creative Arts) láti ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ìlú Èkó.Àwọn eré àgbéléwò rẹ̀ gbogboàwọn ipá àti àmì ìdánikí tí ó ti gbàáwọ́n ìtọ́ka síàwọn ìjásóde wọlé ọjọ́ Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1984àwọn ènìyàn alààyẹ̀.. | wikipedia | yo |
bitcu (Btsc, bitkoin ni gbolohun Yoruba) jẹ owoníná onisisewonkopamọ́ iru owo kika ori komputa kan.. | wikipedia | yo |
O jẹ owoníná ori Kọmputa alainiolùgbà-arin ti ko ni banki agba-arin rara ti ẹnìkan le fun ẹlomiran lori ẹrọ Kọmputa alásopọ̀ ọ̀rẹ́position lai si ẹnìkankan ni arin wọn.. | wikipedia | yo |
Awọn Kọmputa alásopọ̀ nodes lọ un ṣe ìjẹẹri awọn ìdúnàádúrà to unṣẹlẹ pẹlu iṣẹamiganpamọ́ ti wọn jẹ kikọ sinu iwe-akọọlẹ pipinkiri to han si gbogbo eniyan ti a un pe ni Blockchain.. | wikipedia | yo |
bitcu je dida sile latọwọ enikan tabi opo awon enikan ti oruko won daradara satoshi nàka to si je fifi s'ode gege bii ilana iṣisẹ komputa atudìí ni odun 2009.. | wikipedia | yo |
Awon bitin oreúnjẹ dida gege bi ẹ̀san fun igbese Kọmputa ti a un pe ni mining.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ṣe é fi ṣe pàṣípàrọ̀ fún àwọn owóniná míràn, èso-iṣẹ́ àti ìránṣẹ́-iṣẹ́.Ìtọ́kasí àwọn ọ̀wọ́níná oníṣiṣẹ́kókíkópamọ́àwọn owóníná orí kọ̀mpútà.. | wikipedia | yo |