cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
nínú Apocalypse ti Peteru, Pétérù sọ̀rọ̀ pẹ̀lú Olùgbàlà ẹnití “Àwọn àlùfã àti àwọn ènìyàn” gbàgbọ́ pé ó ti pa..
wikipedia
yo
Maniijùism, eyi ti àwọn ìmọ̀ Gnostic ti nfa, tẹrí sí ìmọ̀ràn pé kìí ṣe Jésù, ṣùgbọ́n ẹnìkan ti kàn mọ́ àgbélébù dípò..
wikipedia
yo
Jésù ni ijiyà lori àgbélébù ti wà ni ipilẹ bi ipo ti awọn ohun elo ìmọ́lẹ̀ (Ẹmi) laarin ọrọ dipo..
wikipedia
yo
ní ìbámu sí Bogomilism, àgbélèbú jẹ́ ìgbìyànjú Lucifer láti pa Jésù run, nígbà tí a pe Jésù ní ilé aiyé bí wòlíì, Jésù tìkararẹ̀ jẹ́ ohun tí kò ní ìyípadà tí a kò lè pa..
wikipedia
yo
Bákannáà, Lucifer kùnà àti àwọn ìjìyà Jésù lórí àgbélèbú jẹ́ asán..
wikipedia
yo
gẹ́gẹ́bí díẹ̀ nínú àwọn ẹgbẹ́ Kristiẹni ní ìlú Japan, Jésù Krístì kò kú lórí àgbélèbú ni Golgọta..
wikipedia
yo
Dipo arakunrin rẹ kekere, oluwakiri, gbe ipo rẹ lori àgbélébù, nigbati Jésù sa lọ si Siberia si agbegbe Mutsu, ni ariwa Japan..
wikipedia
yo
Lọ́gán ní Japan, ó di alágbe ìgbẹ, ti gbéyàwó, ó sì gbé ẹbí kan pẹ̀lú àwọn ọmọbìnrin mẹ́ta súnmọ́ ohun tí ó wà ní Shingo bálé..
wikipedia
yo
Lakoko ti o ti ni Japan, a sọ pe o ṣe ajo, kẹkọọ, o si ku ni ọdun 106..
wikipedia
yo
Gẹgẹbi awọn aṣa ti akoko naa, awọn egungun Jésù ni a kojọpọ, ti a fi ṣọkan, ti a si sin wọn sinu ibiti..
wikipedia
yo
Tún múṣọ̀mù kan wà ní ìlú Japan tí ó sọ pé ó ní ẹ̀rí ti àwọn ètò wọ̀nyí..
wikipedia
yo
ní Yazidism, a kà Jésù sí bi "nọmba ti ìmọ́lẹ̀" ti a ko le kàn mọ àgbélébù..
wikipedia
yo
Itumọ yii le gba lati Al-Qur'an tabi awọn Gnostics.ni aworan, awọn aami ati awọn ifarahan niwọn awọn àgbélébù ti Jésù, àgbélébù ti di a bọtini ano ti Christian symbolism, ati awọn àgbélébù si nmu ti a bọtini ano ti Christian aworan, fifun ni jinde lati kan pato ọna awọn akori bi ECce Homo, The igbega ti awọn Cross, ayalu lati àgbélébù ati iparun ti Kristi..
wikipedia
yo
Awọn àgbélébù, ti a ti ri lati Cross nipasẹ Tissot gbekalẹ ni imọran kan ni opin ti ọdun 19th, ninu eyiti a ti ṣe apejuwe àgbélébù ni oju ti Jésù..
wikipedia
yo
Àwọn aami ti àgbélébù ti o jẹ loni ọkan ninu awọn aami Kristiẹni ti a gbajumọ julọ ni a lọ lati igba akọkọ Kristiani ati Justin Martyr ti o ku ni 165 ṣe apejuwe rẹ ni ọna ti o ti tẹle tumọ si lilo rẹ gẹgẹbi aami, biotilejepe àgbélébù han nigbamii..
wikipedia
yo
Àwọn olùkọ́ bíi Caravaggio, Rubens àti Titian ti ṣe àfihàn ipò àgbélèbú nínú iṣẹ́ wọn..
wikipedia
yo
Dedions ti o da lori ilana ti a kàn mọ àgbélébù, ati awọn ijiya ti Jésù tẹle awọn Onigbagbọ pupọ..
wikipedia
yo
Awọn Stations ti àgbélébù tẹle awọn ipo diẹ ti o da lori awọn ipele ti o waye ninu àgbélébù Jésù, lakoko ti o ti lo Rosary ti awọn Ẹmi Mimọ lati ṣe àṣàrò lori ọgbẹ Jésù gẹgẹbi apakan ti àgbélébù..
wikipedia
yo
ati nọmba kan ti awọn Marian compenons tun múdání niwaju Virgin Virgin Mary ni Calvary, fun apẹẹrẹ, Pope John Paul II sọ pe "Maria wa ni ara mọ Jésù lori àgbélébù"
wikipedia
yo
Àwọn iṣẹ́ tí a mòye ti íṣe ti Kristiani nípasẹ̀ àwọn alákọ́so bíi Rphael (fun àpẹẹrẹ, World Crucifixion ), àti Caravaggio (fun àpẹẹrẹ, ìdáwọ́lé rẹ) fi han Virgin wúndíá gẹ́gẹ́bí apákan ti ibi ti a kàn mọ́ àgbélèbú..
wikipedia
yo
Dismas ati gestas, awọn ọlẹ meji ti a kàn mọ àgbélébù pẹlu Jésù Awọn apejuwe Kristiani ni ibẹrẹ ti àgbélébù ipaniyan Odi ibojì akara ti àgbélébù ajọdun ọkan mimọ aye ti Jésù ninu Majẹmu Titun Maria miiran meje Ajogún ti o wasiwaju kika Aladi 30Pages with unre; translations..
wikipedia
yo
TaCO Herming (Filip Tádélọpọlọpọusz SzmàálniaK, Ọjọ́ìbí 29.07.1990) jẹ́ akọrin àti òsèré ọmọ orílẹ̀-èdè Ara Póikùn.Ìtọ́kasí Ara Póikùn00..
wikipedia
yo
Articles with Hcardsgbemi Olateru Olagbegi je olugbohunsafefe Naijiria ni the Beat 99.9 FM (o fise sile ni osu kejila 2021), otaja ati olubagbesafefe “Off-Air with Gbemi & Toolz” adarọ ese..
wikipedia
yo
Gbemi ni omoomo Olowo ti Owo tele sir Olateru-Olagbegi II KBE..
wikipedia
yo
Ni 2008, Gbemi yege gege bii eniyan lori afẹfẹ ti odun naa ni Future Awards Africa..
wikipedia
yo
láìní bàtà tí a ṣẹ̀dá fún àwọn obìnrin tí ó ní àwọn ìṣòro láti ra ìwọ̀n bàtà tó tọ́..
wikipedia
yo
Ni igbejade karun ti ọsẹ Arise Fashion Week, Eko ni ọdun 2018, Gbemi rin fun FIA Factory..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2019, Gbemi di ọkan ninu awọn oju lati Megalectrics Ltd fun Remy Martin.igbesi aye ibẹrẹ a bi Gbemi ni Oṣu Keje ojo kejidinlogun, ọdun 1984, fun Banke ati Yemi Olateru-Olagbegi ni Ile-iwosan St..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé Pampers Private, Surulere, The Ile-iwe girama Nigerian Navy, Ojo laarin 1993 sí 1997 lẹhinna, o tẹsiwaju ẹkọ girama rẹ ni Queens College, Yaba nibiti o ti pari ní ọdún 2000..
wikipedia
yo
Ninu ìmọ̀ ibaraẹnisọrọ ní Oakland University, Rochester ati MSc..
wikipedia
yo
Nínú ìmọ̀ òun ìsọ̀jáde àti ìbáraẹnisọ̀rọ̀ láti Pan-Atlantic University, Èkó .Isẹ́ igbohunsafẹfẹ lẹ́hìn ilé-ìwé, Gbemi ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́bí ọmọ ẹgbẹ́ ti àwọn Ọ̀DỌ́ ní Nigerian Television Authority, NTA 2 ikani karun, Victoria Island ṣaájú kí ó tó lọ sí Cool FM, Nàìjíríà ní 2005 níbi tí ó ti gbàlejò ètò Good Morning Nigeria pẹ̀lú olóògbé Dan gbánu fún ọdún kan..
wikipedia
yo
Ni 2006, Gbemi gbalejo Midday Oasis titi di 2009 nigbati o kuro ni Cool FM losi The Beat 99.9 FM..
wikipedia
yo
Gbemi je igbakeji oludari eto ni Beat FM lati 2011 titi di 2016 ati oludari eto ni ile-iṣẹ-arabinrin, Naija FM 102.7 lati 2011 di 2017..
wikipedia
yo
O fi redio silẹ ni Oṣu kejila ọdun 2021.iṣẹ iṣowo o jẹ otaja tẹ̀léńtẹ̀lé..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2015, Gbemi ṣe ipilẹ laini bata rẹ, Gbemisoke shoes, erongba ti o jade lati inu iriri re nigbati o ba n ra bata.ise ori itage Gbemi kopa ninu ere agbelewo fun igba akoko ni 2017, ninu ere tẹ̀lélen ayelujara ti a mo si Our Best Friend's Wedding..
wikipedia
yo
O kopa gege bii Kemi ninu ere ololufe lati owo The Naked Convos in Collaboration with RedTv..
wikipedia
yo
nípasẹ̀ ìlúd, Adébọ́lá Olowu, Chris Attoh ni àwọn onsere pataki tí ó wà nínú eré náà tí wọ́n ṣe fún sáà méjì..
wikipedia
yo
Ní 2020, ó ṣeré nínú eré àgbéléwò kukuru míràn láti ọwọ́ The Naked Convos tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ Heaven Baby.TNC lẹ́hìn tí Gbemi Olateru-Olagbegi kúrò ní rédíò ní Ọjọ́ 24 ti Oṣù kejìlá, Ọdún 2021..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí olùdásílẹ̀ àti olùpilẹ̀ṣẹ̀ aláṣẹ ti ọ̀kan lára àwọn ìpilẹ̀ṣẹ̀ eré ìnàjú ní Áfíríkà, TNC Africa..
wikipedia
yo
TNNC Africa jẹ ayo ti o ni idojukọ oni-nọmba ati ile-iṣẹ iṣelọpọ fiimu..
wikipedia
yo
Osu kini odun 2021 ni Olawale Adetula ati Daniel Aideyan se igbekale re.Ìgbésí ayé ara ẹni Gbemi je ara idile oba Olagbegi ti Owo, Ipinle Ondo ..
wikipedia
yo
Oni arakunrin mẹta, Olatokunbo Olateru-Olagbegi, Bbukunyi Olateru-Olagbegi ati Adenola Olateru-Olagbegi, o si ti igbeyawo aladun pẹlu Femisoro Ajayi.Ami Eye the Future Awards 2008 - "Eniyan ori afefe ti Odun”
wikipedia
yo
O tun gba ami eye dynamix fun Olùgbékalẹ̀ Redio ti ọdun 2008..
wikipedia
yo
Ó tún gba àmì ẹ̀yẹ “Green Awards for Excellence” fún ẹ̀ka rédíò lọ́dún kan náà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2009, ó gba Ààmì-ẹ̀yẹ “Ìyáàfin Alarinrin ti ọdún” fún “Olufohunsi Rédíò obìnrin tí ó dára jùlọ” àti ní ọdún 2010, wọ́n tún yan lẹ́ẹ̀kansi fún “The Future Awards”
wikipedia
yo
Festus Oluwọle Segun je omo bibi ilu Ijebu Ode, ti won bi ni (20 March 1915)..
wikipedia
yo
Ni o jẹ Bíṣọ́ọ̀bù Anglican .O lọ si Ile-ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ (Our Saviour's Primary School) ní ìlú Ijebu-Ode, ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama (St..
wikipedia
yo
Andrew's College) Ní ìlú Ọ̀yọ́ àti Fourah Bay College, Sierra Leone.Wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bi Díákónì Ìjọ Anglator ní ọdún 1951, bákan náà ni wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí olùsọ̀t ní ọdún 1952..
wikipedia
yo
Ó di ipò yí mú ní ilé ìjọsìn ti Ebute Metta, Arolọ́yà àti ilé ìjọsìn ti Yábàá 1956-1960..
wikipedia
yo
Ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa Union Theological Seminary in New York City, ṣájú kí ótó di Olùkọ́ ní St Augustine’s College, Canterbury..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó padà sí ìlú Èkó, wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà fún Cathedral Church of Christ, Lagos, ó di ipò yí mú títí di ọdún 1970 nígbà tí ó dépòbishop ní apá Gúsù Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n gbe padà sí ìlú Èkó ní ọdún 1975.Àwọn àkọsílẹ̀ àwọn Ọjọ́ìbí ní 1915..
wikipedia
yo
Shaikh Hassan Ahmad Záruq (PAkátà) jẹ́ Afaa àgbà, Onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ẹ̀sìn Mùsùlùmí, Ọmọ Bíbí Ìlú Ìlọrin..
wikipedia
yo
Wọ́n bí ní agbolé oníkàn ní àdúgbò pákátà ní ìlú Ìlọrin ní ìpínlẹ̀ Kwara ní (18th August 1957).Àwọn òbí rẹ orúkọ bàbá rẹ̀ ní Alhaji Ahmad Záruq tí orúkọ ìyá rẹ̀ sì ń jẹ́ Hajia Asmah..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ̀ jẹ́ Mùsùlùmí tí ó sì nífẹ̀ẹ́ sí gbogbo ẹni tí ó bá jẹ́ onímọ̀, yálà nínú ẹ̀sìn ni tàbí ìmọ̀ tó ṣe pàtàkì mìíràn, tí ó sì ma ń sapá rẹ̀ láti ràn wọ́n lọ́wọ́ nígbà gbogbo pẹ̀lú ọ̀wọ̀ àti ìgbìyànjú rẹ̀..
wikipedia
yo
Bákan náà, Alhaji Ahmad Záruq tún jẹ́ oníṣòwò tí ó lààmì-laka nínú iṣẹ́ aṣọ ìbílẹ̀ aṣọ òfì tàbí aṣọ òkè..
wikipedia
yo
Wọ́n fi Alhaji Ahmad Záruq joyè bàbá Adini àkọ́kọ́ ní mọ́sálásí baba pupa ní àdúgbò pákátà ní ìlú Ìlọrin..
wikipedia
yo
Nígbà tí ìyá rẹ̀ Sjia asmah náà jẹ́ gbajúmọ̀ nípa kí a BỌ̀WỌ̀ fún ọkọ̀ nílẹ̀ àti níta.ètò ẹ̀kọ́ OVkh Hassan ZáruQ bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ Lárúbáwá (Arabic School) nínú ẹ̀sìn Musulumi ní ilé-kéwu tàbí agbó òwà rẹ̀ ní paka iyen Shaikh Suleman eni tí o ko ni kika òKEbépọ̀ kí o tó lọ sílẹ̀ Èkó of Shuhu Arabic Arabic), paKata.. PA HDOA iriń ní paKata ní PAnilé lati pa Kata tí o ko ní ẹka ní ó t ni ó t ní ilé fu ní ọdún rẹ̀ * lati ẹni ni sí ẹni * * ní ilé ẹ̀hu * fún ọọdún ní ọdún rẹ̀ ní ó ẹ̀ka ní ó pe ẹka ọdún rẹ̀ ní ọdún rẹ̀ ní pa ní ọdún gbogbo lati pa ní pa ní ọkọ̀ tí ó kọ́ ní ọdún náà kan kan * sí ọdún rẹ̀ ní ilé rẹ̀ jẹ́ pẹ̀lú ọdún rẹ̀ ní pa ní ọdún York ni ní ó yẹ ní o tí ó ti sí ọdún rẹ̀ ti pa pẹ̀lú ọdún tí pa ní sí ìlú * rẹ̀ fún ọdún tí o kọ́ ní ẹ Hassan ( ọdún * ní ilé ọdún ẹ̀ka we ọmọ ní pa ní pa ọdún ní o kọ́ ní kíka tí ó kọ́ ní
wikipedia
yo
Leyin ti o pari nile-eko yi, baba re mu lo si ile-eko MarKazu Ta'Diwaye ‘Ara Al-Islami, Ile-eko ti o je agbon-ọgbẹ ile imo esin Musulumi ni ilu Agege labe akoso Afaa agba sheik Adam Abdullah Al-Ilory fun itẹsiwaju Eko..
wikipedia
yo
Látàrív ìdí èyí, ó kópa nínú ìdániẹ̀kọ̀ọ́ tí Fásitì Madinah, ẹ̀ka ti Ìpínlẹ̀ Kano gbé kalẹ̀ ní àsìkò ọdúnòrìṣà.Ìkẹ́kọ̀ọ́ sùúfí àti àṣeyọrí reshaikh Hassan Ahmad Záruq kẹ́kọ̀ọ́ nípa Súfì lojú ọ̀nà Swyah, láti ọ̀dọ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èni òrìṣà tí wọ́n lààmì laaka láàrín àwọn Afaa Mùsùlùmí..
wikipedia
yo
Lára wọn ni Sheikh Abubakr Sidiq Agbáríma, Sheikh Muhammad TúKur BN Amiinúd..
wikipedia
yo
Ìlànà síṣe sùúfí rẹ̀ ni ó ràn-án lọ́wọ́ jùlọ láti lo òfin àti ìlànà ẹ̀sìn Mùsùlùmí láì yan ìkan ní posin..
wikipedia
yo
Ó dá agbo sùúfí tirẹ̀ náà sílẹ̀ tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní "Zwiwyah dàrú Salwẹm" Ní Ajélọ́gọ̀ Ketu Mile2 ní 1980s,àti Labora ní ọdún 1999 ní Ìpínlẹ̀ Èkó, tí ó sì tún fi lọ́lẹ̀ ni Modinatu dàrú Salã Okolọ́wọ́ Abodún 2006..
wikipedia
yo
Zawi yi sọ ọpọlọpọ awọn Mudam lati igba naa titi di oni ti wọn dipo pataki mu ninu agbo Tijaniyyà.Awon ọrẹ re Shaikh Hassan ni opolopo latari iwa ikoni mora re ati ìbáṣepọ̀ to dan moran pelu ìtẹríba re fun tọmọde Tàgbà lai wonlo tabi eya kan kan..
wikipedia
yo
Látàrí àwọn ìwà ọmọlúàbí rẹ̀ yí ni ó ṣe di ọ̀rẹ́ pẹ̀lú Sheikh Nurud kìgérá, Shaf Muhammad KaBirr B..
wikipedia
yo
Muhammad, ọ̀kan lára àwọn àrọ́mọdọ́mọ ÀnỌbì Muhammad(Saw).Ẹ̀wẹ̀, lórípá ìlànà Tijaniyyah, sheik Ahmad Hassan Záruq dé ipò qutbul FMa tí ó túmọ̀ sí (custo of the Luminous kankan), ní èyí tí ó jẹ́ ipò tí ó ga jùlọ ní ojú ọ̀nà náà, tí ó sì tún wà ní ipò Báq Tulid tí ó túmọ̀ sí (The ríransor of the Imamship
wikipedia
yo
Awon ipo wọ̀yí o du ro fun papin imo ati ilana fun kati dari esin pelu ìmọnà re.dida ile-eko re kaleshaikh Hassan Ahmad Záruq paKata da ile-eko Larubawa tire ti o pe ni Markaz darus Salga Arabic Islamic 1955l, Markaz darus Salga lita'Ali 'Ara Al-Islami ni odun 1982..
wikipedia
yo
Joke Muyiwa je osere ori itage Yoruba , ati okan lara awon oluko ile-eko ititti Olabisi OnaBanjo ni ẹka ere ori-itage..
wikipedia
yo
O gba ami eye oṣere ori-itage to peregede julọ ni Nollywood, elekaarun iru rẹ ( 5th Best of Nollywood Awards), fun ipa ribiribi ri o ko ninu ere aladun kan ti akole re n jẹ Aroko, ti oṣere Femi Adebayo dari rẹ.Awon itọka síàwọn ìjásóde Joke Muyiwa on IMD awon eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Joke Muyiwa je osere ori itage Yoruba , ati okan lara awon olukọ ile-eko fasiti Olabisi Onabanjo ni ẹka ere ori-itage..
wikipedia
yo
O gba ami eye oṣere ori-itage to peregede julọ ni Nollywood, elekaarun iru rẹ ( 5th Best of Nollywood Awards), fun ipa ribiribi ri o ko ninu ere aladun kan ti akole re n je Aroko, ti osere Femi Adebayo dari rẹàwọn itọka síàwọn ìjásóde Joke Muyiwa on IMD awon eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Yábàá Higher College ni wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 1932 ní Yábàá, ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàjíríà léte àti fún àwọn ọmọ ilẹ̀ Adúláwọ̀ ní ẹ̀kọ́ gíga, pàá pàá jùlọ nípa ẹ̀kọ́ ìmọ̀ iṣẹ́ ọwọ́ àti ìmọ̀ nípa iṣẹ́ ìkọ́ni..
wikipedia
yo
lẹ́yìn tí wọn bá tìkọ̀ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yanjú tán ni wọn yóò gbáwọn tí wọn yóò sì gbé wọn lọ sí Fásitì Ìbàdàn ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1948, wọ́n yí iké-ẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ náà padà dí ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ìmọ̀ ẹ̀rọ, ìyẹn Yaba College of Technology.Ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ náà Yaba Higher College jẹ́ ọgbọ́n àtinúdá ọ̀gbẹ́ni E.R.J..
wikipedia
yo
Hussey, ẹni tí ó padà di alákòóso ètò-ẹ̀kọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà (Director of Education in Nigeria) ní ọdún 1929..
wikipedia
yo
Nígbàbtí dépò yí tán ni ó tẹ́ pẹpẹ ilé-ẹ̀kọ́ àgbà Yábàá, gẹ́gẹ́ bí ó ṣe ṣe àgbékalẹ̀ irú ètò yí ní Makerere College ní Uganda ní ibi tí wọ́nb ti gbe wá sí orílẹ̀ èdè Nàjíríà..
wikipedia
yo
Ìdí pàtàkì tí wọ́n fìgbà OVeni yìí ni wá láti kọ́ àwọn amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ ìjọba àti àwọn àdáni , kí ètò-ẹ̀kọ́ lè dàgbà sókè tó ti Fásitì ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Ọ̀gbẹ́ni Hussey bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ láti ilé-ìwé ìmọ̀ ìṣègùn King's College"
wikipedia
yo
Lásìkò ọdún 1932, ilé ẹ̀kọ́ náà ti ní àwọn ìtara ìkẹ́kọ̀ọ́ tirẹ̀, pẹ̀lú àwọn ìmọ̀ àfikún kọ̀ọ̀kan...
wikipedia
yo
Níbà tí wọ́n ti ń kọ́ni nímọ̀ràn iṣẹ́-ọwọ́ tó fi mọ́ ìmọ̀ iṣẹ́ àgbẹ̀, aṣọ́gbó, ìṣègùn, ìtọ́jú ohun ọ̀sìn, ìwọnlẹ̀, àti ìmọ̀ iṣẹ́ àmúṣe ibùjókòó-múlò èrò èrò..
wikipedia
yo
Bákan náà ni wọ́n fún àwọn olùkọ́ ilé-ẹ̀kọ́ ọlọ́dún mẹ́fà onípele kejì(Secondary school teachers) ní ìdáni lẹ́kọ̀ọ́ pàá pàá jùlọ nínú ìmọ̀ syensi..
wikipedia
yo
Ilé-ẹ̀kọ́ Yábàá yí ní agbègbè ìkọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ fún Fásitì ilẹ̀ Lọ́ndọ̀..
wikipedia
yo
Èyí nìwé ìròyìn yí fi ń tọ́ka sí àìperegedé ètò-ẹ̀kọ́ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ girama tí kò múná -dóko, tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ jáde ibẹ̀ yóò fẹ́ láti wọn ilé-ẹ̀kọ́ olùkọ́ ti Yábàá..
wikipedia
yo
Àwọn ẹgbẹ́ Nigerian Youth Movement, tí wọ́n jẹ́ alátakò ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ náà ni wọ́n tún padà di ẹgbẹ́ òṣèlú nílẹ̀ Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ náà nígbà tí ilé-ẹ̀kọ́ náà bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1935, àqọn tí wọ́n pọ̀jù lọ nínú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ẹ̀kọ́ náà jẹ́ ìran Hausa, tí aláṣẹ ètò-ẹ̀kọ́ ìgbà náà ìyẹn Morris, ṣe da lábà ní ọdún 1939 wípé kí ilé-ẹ̀kọ́ Yábàá bí láti kọ́ ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ àwọn tí wọ́n wá láti Gúsù ilẹ̀ Nàìjíríà í wọ́n sì di olùkọ́ fún ìgbaradì ètò-ẹ̀kọ́ tó yanrantí nílé-ẹ̀kọ́ girama ní agbègbè Gúsù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́jọ́ iwájú..
wikipedia
yo
Olùdarí Morris tún fi kun wípé kíkọ́ àwọn ará Gúsù ilẹ̀ Nàìjíríà lẹ́kọ̀ọ́ gidi nílé-ẹ̀kọ́ Yábàá, kí wọ́n lè dara pọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọn láti Ìlà-Oòrùn níbi ètò ìgbani ṣiṣẹ́ ìjọba..
wikipedia
yo
Awon aláṣeẹ miiran tun so Qipe ise ka naa ni ile-eko Kaduna College..
wikipedia
yo
Yóò ṣe bí ti Yábàá tàbí kí ó ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ .Látàrí àìfẹsẹ̀ rinlẹ̀ ètò ìlànà ẹ̀kọ́ Yábàá College láwọn àsìkò kan, àwọn omilẹgbẹ akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n ń wá láti wọlé sílé-ẹ̀kọ́ Fásitì ni wọ́n lọ aí ilé-ẹ̀kọ́ Fourah Bay College ní orílẹ̀-èdè Sierra Leone, tàbí kíbwọ́n lọbsí orílẹ̀-èdè USA tàbí hnfted Kingdom tí wọ́n bá lọ́wọ́ọ́wọ́ .ní 1948 wọ́n gbé ilé-ẹ̀kọ́ Yábàá síwájú aí ibi tí wọ́n sì sọọ́ di University College of Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Wọ́n gbé Yaba College of Technology, dìde ní ọdún 1947 níńgba Yaba Higher College, tíbwọ́n sì sọọ́ di ìpele ẹ̀kọ́ kejì lẹ́yìn ilé-ẹ̀kọ́ girama ọlọ́dún mẹ́fà èkejì, lẹ́yìn Fásitì ìlú Ìbàdàn.Lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ jáde nílé ẹ̀kọ́ náà t..
wikipedia
yo
Àlùkò, Novelist Isháyà Audu, Minister of External Affairs (Foreign Minister) From 1979 to 1983 Under Shehu Shagari Stephen Oluwo̩ Awokoya, Minister of Education in the Old Western Region of Nigeria Olumbe Bilr, Sierra Leonean Scientist and Academic Saburi Bíòku, Scholar and Historian, Pro-Chancellor of the Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University.
wikipedia
yo
Akintola deko, Minister for Agriculture in the Western Region of Nigeria Joseph Chike Edozien, Traditional Ruler of Clau, Nigeria in Delta state Odidíà, Oba of Benin Samuel Fawehinmi, òṣùpáring Nigerian furture Magate eni Njoku, first vice-Chancellor of the University of Lagos and later Vice-Chancellor of the University of Nigeria Michael Okpara, Premier of Eastern Nigeria during the first Republic, from 1959 to 1966 ayo Rosiji, Poliji, Statesman and former Minister for Health and Minister of Information Shehu Shagari, President of the Nigerian Second Republic (1979-1983) Tunji Soyọnu, Nigeria-born UK Lawyer and musician Joba Waschuku, First Nigerian Ambassador and permanent Representative to the United Nations Akintola Williams, Chartered Accountant, Founder of the Nigerian Stock Olúwa and the Institute of Chartered Accountants of Nigeria Frederick Rotimi Williams, The first Nigerian to become a senior advo of Nigipanṣágà Ika si awon iwe Pages with unre; translations
wikipedia
yo
Folake Folarin-Coker (tí a bí 1974) jẹ́ onísẹ́ aṣaṣọlẹ àti ti olùdarí tí Tiffany Amber..
wikipedia
yo
Lẹhin Eko rẹ ni Switzerland ati Ilu United Kingdom, o gba oye ile-iwe giga ninu imọ-ofin eporọ̀bi..
wikipedia
yo
Folake pada si orile-ede Naijiria lati tẹsiwaju ninu iṣẹ Asaaṣọ "Tiffany Amber", ẹya ise eso-aṣọ ti Folake ni a filole ni ọdun 1998 ni Ilu Eko..
wikipedia
yo
ó ti ṣe ìfihàn ẹ̀ṣọ́-asọ̀ ní Africa, Europe àti United States..
wikipedia
yo
ní ọdún 2008, ó jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ Aláwọdúdú tí ó ma fi eso-aṣọ han ni New York Fashion . Folake wo Iwe-itan gẹgẹ bi ẹni akọkọ ti o gba Aami Eye Oníṣẹ́ "Designer of the Year" ni ibi ifihan A"frican Fashion Week" ni Johannesburg ni ọdun 2009 ati ami ẹyẹ tun tun "Fashion Brand of the Year" ní ibi ifihan eso-aṣọ Iwe irohin Arise Magazine ni 2011..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2013, ó gba àmì ẹ̀yẹ fún oníṣòwò t'ọ́n-túkò ní Women, Inspiration and Enterprise (WI) Odposidele, sì ṣe àkójọ àwọn obìrin Forbes Power..
wikipedia
yo
ó fi ìforóhan rẹ̀ ‘Nirvana' fún àwọn orísun omi / ooru ní dọii àwọn ìfilọ́lẹ̀ àwọn àṣà..
wikipedia
yo
Coker jẹ́ ìyàwói oníṣòwò fọ́ọgu Coker, ẹnití ó ti ṣe ìgbìmọ̀, olùdarí àkóso ìṣàkóso ti àwọn nọ́mbà ti àwọn Ọjà-àṣẹ ti Ìpínlẹ̀ Èkó, bayi oluranlowo Ìran sí Gómìnà ti Lagos..
wikipedia
yo
àwọn Ọjọ́ìbí ni 1974àwọn ènìyàn Alààyègun With unredid translations..
wikipedia
yo
Festival jẹ orukọ ọkan ninu awọn ede ti a sọ ni South Asia..
wikipedia
yo