cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
A máa ń fi ìrù sí ọbẹ̀ láti fi jẹ kí ó ní adùn àti òórùn dáadáa.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọbẹ̀ ti a lè fi irú si ni ọbẹ̀ ila, ọbẹ̀ ewédú, ọbẹ̀ ẹfọ, ọbẹ̀ ata, ọbẹ̀ ẹ̀gúsí, ọbẹ̀ Ọ̀nọ̀no ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Irú ni ilẹ Yoruba pin si oriṣi meji, irú woro àti ìrú pẹ̀tẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ṣùgbọ́n irú wóró máa ńdúró sínú ọbẹ̀ nítorí pé ọ̀lẹ.Irú jẹ́ èròńjà ọbẹ̀ tó ṣara lọ́rẹ.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọmọ ilẹ̀ Yorùbá ni ìgbàgbọ́ pé irú ni àǹfààní ti on ṣe fún ojú lọ́pọ̀lọpọ̀.. | wikipedia | yo |
Nítorí èyí, wá máa sọ fún ẹni tí ojú dùn kí ó má jẹ ìrù dáadáa.Àkíyèsí irú ni pé ó gbọdọ̀ kún fún iyọ̀ kí ó bá lè pẹ́ nílẹ̀.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ọ̀gbìnàwọn onjẹàwọn ohun ọ̀gbìn jíjẹ.. | wikipedia | yo |
Ọbẹ̀ yó jẹ́ orúkọ àwọn ọbẹ̀ tó máa fà tíkò tàbí yọ lọ́wọ́.. | wikipedia | yo |
Bi apejuwe ọbẹ̀ ila, ọbẹ̀ ewédú, ọbẹ̀ Ọ̀gbọ̀nọ̀ tàbí èyí tí a no sí àpọ̀n.. | wikipedia | yo |
Ọbẹ̀ yọ̀jẹ́ ọbẹ̀ tó wọ́pọ̀ ní apá àríwá ìwọ̀ irun àti apá àríwá búṣú ọrun ní ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ìrísí ọbẹ̀ yí máa ń ki, yó sì má yóbọ̀lọ̀ tí a bá ńjẹ yálà pẹ̀lú ṣíbí tàbí pẹ̀lú ọwọ́ wa.Àwọn oúnjẹ tí an fi jẹ ọbẹ̀ yó ni an pè ní òkèlè.. | wikipedia | yo |
Awon ounje bi fùfú, iyán, àmàlà, ẹ̀bà, ati bee bee lo.Awon itọkasi.. | wikipedia | yo |
François Henri "Jack" Lalanne (September 26, 1914 – January 23, 2011) jẹ́ òṣèré ara Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré tẹlifíṣàn ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Štefan Karl Stesson (July 10, 1975 – August 21, 2018) jẹ́ òṣèré ara Islánsan.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré tẹlifíṣàn Ara Islándìàwọn Ara Islándì.. | wikipedia | yo |
Hervé Jean-Pierre Villechai (April 23, 1943 – September 4, 1993) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.ìtọ́kasí àwọn òṣèré fíú ará Amékawọ́n òṣèré tẹlifíṣàn ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Magnus orn eyjolfsson scheving (November 10, 1964) jẹ́ òṣèré ara Islándì.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú Ara Ara Isdiàwọn Ara Islándì.. | wikipedia | yo |
Caroll Edwin Spinney tí a bí lọ́jọ́ mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n, Oṣù Kejìlá Ọdún 1933,dágbére Lota ní ọjọ́ kẹjo Oṣù Kejìlá Ọdún 2019 (December 26, 1933– December 8 2019) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Gudmundur Thor Korun (June 14, 1974) jẹ́ òṣèré Ara Islándì.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn òṣèré tẹlifíṣàn Ara Islándiàwọn Ara Islándì.. | wikipedia | yo |
New Money (Owó Tuntun) je ere ori ero mohunmaworan ni ilu Amerika ti o bo s'ori afefe ni ojo kokan-din-lọgbọn osu karun odun 2015 l'ori ero ayelujara mohunmaworan e! | wikipedia | yo |
Èrè yí tí a pín sí abala mẹ́fà dá l'órí bí àwọn tí ó l'oró púpọ̀púpọ̀ ṣe ma ń ná owó wọn àti irú ìgbé ayé tí wọ́n ma ń gbé.. | wikipedia | yo |
Ile ise mohunmaworan Leftfield ni o se agbekale ere naa.Ere yi bo s'ori afefe ni ilu Amerika ni ojo kokan-din-lọgbọn osu karun odun 2015 si oju kopa awon eniyan ti o to okòó le ni'gba o le ẹyọ kan.. | wikipedia | yo |
Ni akoko ti ere yi bo sori afẹ́fẹ́, eniyan ti o to egberun lona meta-le-lẹ́gbẹ̀sán ni o ja kuro loju iwọ ere yii ti a pe ni lead-in the Soup.. | wikipedia | yo |
Ni ìlú Australia, eré yi bọ́ sórí afẹ́fẹ́ ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹfà ọdún 2015 lórí ẹ̀ka ẹ̀! Ní ìlú Australia… | wikipedia | yo |
Addison Jayne Timlin (ojo ibi ojo kokan din logbon, osu kefa,odun 1991) je osere binrin omo ile Amerika ti a mo si Kami lerner ninu ere (Ilu ti ko fe ki oorun wo) The Town that dreaded sundown (2014) ati Colleen Lundasford ninu ere Little Sister (ọmọbirin kekere) (2016). A mo fun ipa rẹ gege bi Sasha Bingham ninu igba afihan) Showtime’ s Californication. She is also known for playing Sasha Bingham in Showtime's Californication.Iṣẹ́ òòjọ́won bi ni Filadéfíà, peniSilafaníà, Timlin jade ni amohunmaworan gege bi Amy, omo odun merinla ti o ni arun ito suga, in the 2005 film Alayoiled Adam Clive Owen and Melissa George, who played her parents.. | wikipedia | yo |
Timlin played maddy in a short film, The Isabel Fish, directed by Lara Zic for the Columbia Film Festival.. | wikipedia | yo |
In 2007, Timlin appeared in the music video, "SAAAls Lessons," by Albuquerque, New Mexico based indie-rock band, The Shins.. | wikipedia | yo |
In 2008, she made an appearance in the music video for the song Check Yes Juliet by we the Kings, playing the fictional Juliet.. | wikipedia | yo |
She was cast in the short-lived CBS television drama, 3 lbs, as Charlotte Hanson (the daughter of the main character played by Stanley Tucci), in three of the eight episodes that were filmed.. | wikipedia | yo |
Timlin is seen in the short film Man, written and directed by Myna Joseph, which was screened at the Sundance Film Festival and at Cannes.. | wikipedia | yo |
In 2008 she played Emily Draper in the ABC Television Show, Cashmere Mafia, the Troubled teenage daughter of Juliet Draper (Miranda Otto).Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1991àwọn ènìyàn AAlààyè.. | wikipedia | yo |
Alhaji Muhammed Raji Alabi Owoníkọ̀kọ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà,olórin àpàlà.Wọn bi Raji ni ìlú Oro ni Ìjọba ìbílẹ̀ Ìrẹ́pọ̀dùn ìpínlẹ̀ Kwara.Àwọn ìtọka síàwọn olórin ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Alhaji Lukman ẹbun Oloyede Ọláìni tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Igwe jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti òṣèré sinimá àgbéléwò.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí ẹ̀bùn olóyè ní ìlú Kenta, Òkè-Ejigbo Abeokuta.ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀yáyá lọ sí ilé ìwé alákọ̀ọ́kọ́bòẹ̀rẹ̀ St.Judes ní ìlú Abeokuta ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, tí ó sì tún tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ìwé girama (Premier) ní Abeokuta.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ti ó parí èyí ni ó lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìbára ẹni sọọ̀rọ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ti Moshood Abiola ojeèré Ìpínlẹ̀ Ògùn.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré_ dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré músíbáù Shodi Shodi ní àsìkò 1970s tí ó wà ní Abeokuta nígbà náà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ẹgbẹ́ akọ́mọlédè àti àṣà Yorùbá jẹ́ agbari-jọ-pọ̀ àwọn olùkọ́ nílé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, girama àti ilé ẹ̀kọ́ Fásitì ti ìjọba pẹ̀lú aládàáni jákè jádò ilẹ̀ Nàjíríà.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀gbẹ́ yìí ń ṣomi Yorùbá níbi ìgbẹ́ láláru èdè, àṣà àti ìdàgbà sókè Confara Conààbò Ìka Gadíru Ofuọn | wikipedia | yo |
Babalola Chinedum Peace (née Anyabuike) FAFA, FAFA wa ninu awon ojogbon omo Naijiria to je inimo nipa egbò igi Pharmacy, to tun je obinrin akoko elegbogi ibile Fasiti ilu Ibadan.Iṣẹ iwadii re da lori àtúpalẹ̀ oogun Drug Analysis (P/PD pharmacogenetics), (pharmacogenomics), (Pharmaceutical Analysis) pelu (BioEthics). ni Adariri agba Faculty of Pharmacy and principal investigator ti University of Ibadan Centre for Drug Discovery, Development and Production.Lára awon idagbasoke to se ni High-performance liquid ríranto ona Itupo quinine ninu bi bi Omeola.. | wikipedia | yo |
ÀGBÉKALẸ̀ yí LÓRÍ GBÉ quinine jẹ́ kí ètò pharmacokinetics ye nípa quinine ní Africans tó fa ipile ìwọ̀n ìwọ̀n bí a ṣe lè mú oògùn ako iba fún aláìsàn.ètò ìwádìí BÍ nkan ṣe ṣe lóríoògùn àti bi àwọn ọmọ ogun ara ṣe ń gba agbára agbára àti bí wọ́n Sr ń loò tí a mọ̀ sí MeAMMema, ní ó mú abá idiwoku wà lórí bi bíailaailawe pẹ̀lú iṣẹ́ ò di ẹwa nínú àwọn antiìkì ní a bá ti a bá àwọn oògùn ele iba.(we pẹ̀lú àwọn ojogbon onímọ̀ onímọ̀ tí ó tọ́ pẹ̀lú ọdún tí ìròyìn àkọ́kọ́ wa gu àkọ́kọ́ kan guGenetic tí ìlera ti àwọn tí àwọn tó ń da àwọn aláì́ ṣse àwọn aláìtu gu-gu-ani'ani) gẹ́gẹ́ bi ibé bí ÌBÉÈRÈ gẹ́gẹ́ tí ẹbu ọdún tí a máa sí ọdún rẹ̀. Ní ọdún ọdún òwà sí ọdún ọdún ohun ohun ọdún ohun pé ohun ẹ̀ni gbogbo obìnrin ní ọdún tí wọ́n bá wọ́n t àwọn ni a máa ọdún àwọn oníràr pẹ̀lú ọdún [mè ohun ọdún àwọn oníka pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀ ní ọdún tí àwọn pẹ̀lú ọdún rẹ̀ lati dá pẹ̀lú àwọn oníṣẹ ọmọ National rẹ̀ ni ó mú ọdún rẹ̀. gẹ́gẹ́ ohun ẹ̀we ohun ti a ti ọdún ogun ti o bá ọdún rẹ̀ sí nkan ijo ò we ọdún àwọn ọmọ ohun ogun rere tí ó fi agbára ọdún ọdún * ní wọ́n * | wikipedia | yo |
Ìròyìn yí mú àwọn ojúlówó àbá wá pé díẹ̀ nínú ọmọ Nàjíríà ní àìsàn (mútant Cyp2C19 genes) àti àìkọbi ara sí iṣẹ́ òwò òògùn iṣẹ́ lọ́pọ̀ (Boasizer).Wọ́n yan Babalola gẹ́gẹ́ bí olórí Gíwá Kejì ní ilé ẹ̀kọ́ Vice Chancellor ti Chrisland University, ní oṣù Belu (November), ọdún 2017,Abeokuta, ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà.References àwọn ènìyàn alààyè.. | wikipedia | yo |
jáir Mesas Bolsọ́nàrọ (ọjọ́ìbí kẹta 21, 1955), lásán bí jáir Bolsọ́nà, ní lọ́wọ́lọ́wọ́ Ààrẹ ilẹ̀ Brasil 38K, lórí aga láti Kínní 1, 2019.Ìtọ́kasí Ara Brasil.. | wikipedia | yo |
"Awakọ̀ òfúrufú" tàbí “Pàdé Múmùlé “Jẹ́ Epir Awakọ̀ Nínú amóhùnmáwòrán Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Àgbégbéjáde ní orí ìfẹ́ Kolérí ní ìdá Amẹ́ríkà (ABC) ní ọjọ́ Oṣù kẹsán ọdún 2012.. * | wikipedia | yo |
olùkọ̀tàn ni Dan Fogelman ,tí adarí sì jẹ́ Chris Koch .eré na kòrí ìwúrí ní àwùjọ ÀPA.eré yìí, alámúleti wáyé láti ọwọ́ Fogelman, ẹni tí ó kó cars (àwọn oko) , cars 2 (àwọn ọkọ apákejì) àti 10d Films(eré Tkò) .. | wikipedia | yo |
Sibẹsibẹ ere apani lerin nii, iwe itan naa fara han gegebi eleyi ti o po fun amohunmaworan mainstream lamerica.. | wikipedia | yo |
Fogelman loyun itan Alamuleti leyin ti o se abewo si iya renigated community . | wikipedia | yo |
ilé iṣẹ́ amóhùnmáwòrán Amẹ́ríkà gbà Epirsórí eré alámúlé ní oṣù kẹwa ọdún pẹ̀lú ìfarasíi.. | wikipedia | yo |
Chris Koch tọwọ́ the show was originally produced for ABC Studios andWarner Bros.. | wikipedia | yo |
Television Was Replaced by company Kaplan Entertainment.. | wikipedia | yo |
Dan Fogelman, Chris Koch, Jeff Morton and Aaron Kaplan executive produced the episode.. | wikipedia | yo |
In may 2012, the show renamed to the Neighbors , and production of the program was green-iweté.. | wikipedia | yo |
9ice, ti oruko re je Alexander AbOlore AdeTímótì Akande (won bi ni ojo ketadinlogun osu ṣẹ́ẹ́rẹ́, odun 1980), o je olorin, ònkọ̀tàn-orin, onijo omo orilẹede Naijiria.. | wikipedia | yo |
O gbajumọ fun Igbedẹyọ rẹ, owe lilo ati agbekale orin rẹ lona ara.Ìdílé olórogún ni 9iceti wa, baba rẹ ni iyawo marun-unati ati ọmọ mẹsan-an ni ilu Ògbómọ̀sọ́, IpinleOyo Oyo ni iwo-oorun Naijiria.. | wikipedia | yo |
Àwọn òbí rẹ̀ ṣe akiyesi ẹ̀bùn orin kíkọ rẹ̀, wọ́n sì gbà á láàyè láti di olórin.Ó ní ìyàwó tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Adétola Anifàlà, Ọlọ́run sì fi ọmọ Jíkììkì wọn.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014, 9ice du ipo lábé Asia All Progressive Congress(APC) láti di aṣojú-sofin nílé Igbimọ Aṣòfin sugbon ko wole ibo.. | wikipedia | yo |
Nínú ìyìn inú-ilé (primaries) ló ti jákulẹ̀.Gómìnà Abiola Ajimobi sì fi jẹ́ olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Gómìnà.Ìsókè 9ice lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ẹ̀ abúlé òkúta àti ilé-ẹ̀kọ́ girama CMS.. | wikipedia | yo |
Kò kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin tí ó lọ ṣe ní Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Èkó, ní ṣe lọ gbajúmọ̀ iṣẹ́ orin tí ó yàn láàyò.. | wikipedia | yo |
O bẹrẹ orin kikọ ni ọdun 2000, o feran Pasuma wonder.. | wikipedia | yo |
Díṣẹ tí ó ń gùn ún láti fi gbé orin rè kalè ní àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àdúgbò rè àti àwọn olórin aṣáájú ti ri ó ri bi àwòkọ́ṣe bíi Ebenezer Obey, King Sunny Ade, Lároko Alamu, olóògbé Aladfìfẹ́rí , àti ologbe Alanirunìyàn Ishola.Ìbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ọdún 1996, ló kọ́kọ́ ṣe rẹ́kọ́ọ̀dù alapejuwe tí ó pè ní risi dé alàgbàja ṣùgbọ́n ọdún 2000 ló tó gbé rẹ́kọ́ọ̀dù àkọ́kọ́ rè tí ó pè ní Little Money jáde.Ní ọdún 2008, 9ice gbe orin góngó aṣọ.. | wikipedia | yo |
Ti orin naa si gbálẹ̀ kaakiri, eyi si mu ki wọn sọ pe ki o wa kọ orin nibi ojoobi aadọrun-un odun Nelson Mandela ni ilu London, United Kingdom ni osu Okudu 2008.. | wikipedia | yo |
O gba ami eye olorin Takasúfèé ti o dara ju lọ ní MTV Africa Music Awards.Góńgó aṣọ náà gba àmì ẹ̀yẹ mẹ́rin níbí 2009 hiphop World Awards tí ó wáyé ní International Conference Centre, Abuja.Ní ọdún 2020, 9ice gbe àwo orin mìíràn jáde tí ó pè ní "TipTi The The Iceberg" | wikipedia | yo |
Oun ni oludasile ati alákòóso iléeṣẹ́ àgbọ̀rín-jade alapomeji Ancelétí rẹCordara rẹ̀ 9ice máa n lo èdè Yorùbá nínú àwọn orin e.. | wikipedia | yo |
Nígbà mìíràn ó ma ń lo àwọn òwe èdè Yorùbá, tàbí kí ó ṣe àmúlúmù pẹ̀lú èdè Hausa, igbó tàbí èdè Òyìnbó.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1980àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
jẹ́ àgbà tẹnis ara tsílẹ̀.Ìtọ́kasí Alexa Guarachi — WTA Tennis {en} Alexa Guarachi — ITF Tennis {en} agba tẹnis ara t .. | wikipedia | yo |
Ile ise olùpèsè oko Innoson ti orile ede Naijiria, ti Eọ̀n we age re si IVM, je ile ise ti o n pese orisirisi ohun àmúrina gege bi oko akero, oko Igba ni orile ede Naijiria... | wikipedia | yo |
Ọjà Àgbàláta (Badagry Market) ni Ọjà tí ó tóbi jùlọ ní agbègbè ìlú Agbadarigi tàbí Badagry.. | wikipedia | yo |
Ọjà yìí ni ó wà ní ìtòsí àwọn ilé ìfowó-pamọ́ UBA,Zenith àti ìfowó-pamọ́ Union.. | wikipedia | yo |
Ọjà yìí ni ó jẹ́ wípé àwọn ẹ̀yà ègún ti ọ̀sẹ̀ òòjọ́ wọn jẹ́ iṣẹ́ oko ṣíṣe, ẹni híhun, agbọ̀n títa àti epo ṣíṣe ni ó wọ́pọ̀ tí ó ń nájà náà.Àwọn ọjà tí ó súnmọ́ àgbàláta àwọn ọjà tí ó súnmọ́ àgbàláta ní Ọjà Àjàrà, rànverekété, àti Ọjà hùntọ̀, ni ó tún súnmọ́ Ọjà àgbáláta ṣùgbọ́n Ọjà àgbáláta ni ó gbajúmọ̀ jùlọ nítorí wípé oríṣiríṣi àwọn ìlú ni ó wà ń ná Ọjà náà,pàápàá jùlọ àwọn ọlọ́jà láti orílẹ̀ èdè Bene ma ń wá láti ná Ọjà náà nítorí wípé omi ọ̀sà tí ó ṣàn wọ orílẹ̀ èdè Bene ti ìlú Àgbádárìgì sì tún jẹ́ ààlà láàrí orílẹ̀ èdè Bene.Ọjà àgbàláta gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà ìdàgbà-sókè àgbàláta gẹ́gẹ́ bí ayé ìpẹ̀jọ́ pọ̀ pọ̀ kan láàrin àwọn ọ̀pọ̀ ẹ̀yà bí ẹ̀yà Yorùbá,igbó,igbó, Yawusa, àti àwọn ẹ̀yà míràn láti ìlú òkèrè ni ó ti mú ọ̀làjú àti ìdàgbà-sókè bá ìlú Àgbádárìgì nípa ètò ọrọ̀ Ajé,ilẹ̀, ilẹ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.àgbékalẹ̀ ètò Ọjà náàwọn ṣe àgbékalẹ̀ ààtò ètò Ọjà náà pẹ̀lú ìbámu àtọ̀ ìlú nípa kíkọ́ ìṣọ́ àwọn ọlọ́jà aṣọ lọ́tọ̀, ìsọ̀ àwọn ẹlẹ́ran lọ́tọ̀, táwọn aláta lọ́tọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Sheik Mujideen Àjàní Bello jẹ́ Afaa nlá oní wáàsí lójú ọ̀nà mùsùlùmí, àti ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn, ó jẹ́ ọmọ àádọ́rin ọdún.Ìgbé ayé RESheik Mujideen Àjàní Bello bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ wáàsí ìta gbangba nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́wàá lẹ́yìn tí ó ti kọ́ nípa ìmọ̀ àlùkùránì lábẹ́ Bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ Afaa àgbà nílùú Agbẹnugbé tí ó jẹ́ ìletò kan nílùú Ìwó.. | wikipedia | yo |
Lásìkò tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́sàán ní ó lọ gbé lófo àbúrò bàbá rẹ̀ tí òun náà náà jẹ́ Afaa oníwáàsí ìta gbangba tí ó sì tún nílé kéwu nílùú Ìbàdàn.ètò ẹ̀kọ́ rẹLẹ́yìn ti Mujadeen dé ọ̀dọ̀ àbúrò bàbá rẹ, ó bẹ̀rẹ̀ ilé ìwé alákọ̀ọ́kọ́-bẹ̀rẹ̀ nígdan, tí ó sì tún ń fojú ṣekóo àlùkùránì ní ìrọ̀lẹ́ tí ó bá dé láti ilé ìwé rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ girama àtifagbára ẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ (N.C.E).. | wikipedia | yo |
Ó sebíṣe Olùkọ́ni ní ilé ìwé Ansa-ru-deen College tí ó wà ní ìlú ṣákì ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.. | wikipedia | yo |
Ó tún ṣe iṣẹ́ olùkọ́ ní ìwé gírámà Abeokuta,níbi tí ó tó kọ́ ẹ̀kọ́ àti ẹ̀kọ́ biology.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ Kurunmikú Ìjiyé jẹ́ jagun jagun, alágbára, akínkanjú àti ọ̀kan lára àwọn akọni ìgbà tí ó ní agbára, ọgbọ́n àti oògùn púpọ̀ púpọ̀.. | wikipedia | yo |
O je omo bibi ati Asiwaju tabi adari ilu Ijaye lasiko tire ni ipilẹ Oyo ni asiko 1831-1862 aye rẹAare Kurun ni o je oníyàwó pupọ ti o si lo opo igbesi aye rẹ loju ogun, nibi ti o ti ma n ja fitafita ti o si n ko opo ẹru ati ẹru.. | wikipedia | yo |
Kurunmi bá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìlú jagun tí ó sì ṣẹ́gun wọn.Ìtagbò rẹ̀ pẹ̀lú Ìbàdànọ̀nà méjì ni ìtàn tí ó rọ̀ mọ́ Ààrẹ Kurunmi Ìjaye tí ó sọkún fa ikú rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àkọ́kọ́ ni wípégẹ́gẹ́ bí ìtàn ṣe sọ, Ààrẹ Kúrunmi kọ ìrẹ́jẹ Ìdí nìyí tí òun àti Aláàfin Ọ̀yọ́ìgbà náà ọba Aláàfin Adélú tí ó jẹ́ ọmọ bíbí Aláàfin àtibárun tí ó gbésẹ̀ fi gbẹ́nà wojú ara wọn látàrí wípé Ààrẹ Kúrunmi kó láti san ìṣákọ́lẹ̀ ọdọọdún fún Ọ̀yọ́.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ Kurunmi fẹ́ láti gba òmìnira fún ìlú rẹ̀ (ÌJÍF) kúrò lábẹ́ àṣẹ àti ìmúni sin Ìlú [Oyo]],ṣùgbọ́n, ọ̀rọ̀ náà kékí púpọ̀.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí Aláàfin Adélú rí wípé Kurunmikú ti tàpá sí àṣẹ àti òfin ìlú Ọ̀yọ́, ó gbé oníṣẹ́ ọba dìde wípé kí wọ́n lò fún ní àrọko méjì kan kí ó mú èyí tí ó wùúfí.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ Kurunmikú àti ìlú Ìbàdàn ni wọ́n jọ dámi ìjà kaná, tí ìtàn sì tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé olùpolongo ẹ̀sìn Kírísítì Olùṣọ́ Àgùntàn Bowen tí ó dá Ìjọ Baptist sílẹ̀ náà bẹ Ààrẹ Kurunmi láti má ṣe jagun, kàkà kí ó gbà ń ṣe ló wọlé lọ gbé Bíbélì àti ẹ̀tù ìbọn jáde tí ó sì ń sọfún òkúsọ náà wípé ogun ni òun yóò mú nítorí jagun jagun ní àwọn baba ńlá òun Báyìí ni Bowen sọfún Kurunmi wípé Ìhìn Rere ni òun wá polówó rẹ̀ kìí sógun, lẹ́yìn èyí ni a gbọ́ pé olùṣọ́ náà kúrò ní Ìjaye tí ó sì lọ dá ìjọ rẹ̀ sílẹ̀ ní ìlú Abeokuta.Èmi sọnù púpọ̀ nínú ogun abẹ́lé Ìbàdàn àti Ììjà yìí tí Ààrẹ Kurunmi Kúrunmi Ìbàdàn fún ìgbà àkọ́kọ́ tí ó sì mú Baṣọ̀run Ogunmọla tí ó jẹ́ olórí ológun ilẹ̀ Ìbàdàn lásìkò náà lẹ́rú, ó sọọ́ mọ́lẹ̀ nídìí ọ̀kan nínú àwọn òrìṣà ògún rẹ̀, tí ó sì ń fún ní eérú (A (A dípò dípò gidi.. | wikipedia | yo |
Ìtàn sọpé ọ̀kan lára àwọn ìyàwó Ààrẹ Kurunmi ni tí ó jẹ́ agbeyin Bebo jẹ ni ó yọ́ kẹ́lẹ́ lọ tu Baṣọ̀run Ogunmọla sílẹ̀ láàrin oru.. | wikipedia | yo |
Kété ti Ogunmọla padà de Ibadan ni ó lọ́ wá àwọn ọmọ ogun kúnra pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ ọgọ́rùún àti mọ́kànlélógójì ìlú (141), láti fi bá Ààrẹ Kurunmi jà.. | wikipedia | yo |
Ninu ogun eleekeji yi ni awon omo Kurunmi maruun ku si, pelu bi awon omo ogun Ibadan ti pa awon omo re maruun ti won si gbe ori okan ninu won ranse si baba won (Ku).. | wikipedia | yo |
Ikú àwọn ọmọ yìí Duun gidigidi.Ikú rẹ̀oríṣiríṣi atótónu ló wáyé lórí ikú Ààrẹ Kurunmimi.. | wikipedia | yo |
Ọ̀pọ̀ ní ń ṣe ní ojú tìí nígbà tí ó pàdánù ogun náà ṣòwò Ìbàdàn tí ó sì fi bínú bẹ́ sínú odò ọ̀sẹ̀, àwọn kan ní ń ṣe ló pokùn so, bákan náà ni ìtàn kan tún sọ pé wọ́n paá lójú ogun tí wọ́n sì gbé òkú rẹ̀ wálé láti SIIN, ṣùgbọ́n wọn kò rí Órípà ibojì rẹ̀ títí di òní, àwọn kan tún sọ pé Ààrẹ Kurunmi kú sínú ilé rẹ̀ ní tí wọ́n sì sin sí ẹgbẹ́ ọ̀dọ́ ọ̀sẹ̀.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún fi kùn wípé ṣaju kí wọ́n tó sin Ààrẹ Kurunmikú, wọ́n kọ́kọ́ sin àwọn ẹrú mẹ́ta ṣáájú kí wọ́n tó sin Ààrẹ Kurunmi níbàámu pẹ̀lú ìṣwó.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Afrominettia jẹ́ ọ̀wọ́ tàbí irúkòkòrò kẹ̀kẹ́ tíeré ó n gúnyẹ̀ẹ́ tí ó sì jẹ́ ẹbí Lauxaniidaeaniidae.Irú tàbíowó owó a.. | wikipedia | yo |
Àmì ẹ̀yẹ lámèyítọ́ Fíímù Nollywood àti ilẹ̀ Adúláwọ̀ jẹ́ ayẹyẹ tí ó ma ń wáyé lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo lọ́dún fún àwọn òṣèré fíímù àti sinimá àgbéléwò nílẹ̀ Adúláwọ̀.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ti ń ṣe rí ní orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà láti ìgbà tí wọ́n ti dá sílẹ̀ láti ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù Kẹ́jọ́, ọdún 2011 (September 17, 2011).. | wikipedia | yo |
Ayẹyẹ ami eye yii ti ẹlẹ́keerin iru rẹ̀ waye ni ojo ketala osu Kẹ́sà, odun 2014 (13 September 2014) ni gbogàn sinínma Saban,Beverly Hills, ni California.Irú rẹ̀ ẹlẹ́kẹfà waye ni ojo kokandinlogun osu kokan odun 2016 ni gbogàn Ceregbo was held on November 19 at Alex ,Glendale, California.. | wikipedia | yo |
Iisọdọtun Nollywood tabi Nollywood Reinvented, ti a tun mọ si NR, jẹ pèpéle ero ayelujara ti won da sile ni odun 2011, pèpéle yi wa fun Pori awọn fiimu ati sinima ọlọkàn o kan. O tun funi ni awọn awọn fiimu, awọn oṣere, ati awọn eniyan miiran pẹlu.. | wikipedia | yo |
Oun ni iru re akoko ti yoo kọkọ bẹrẹ Ifufe iṣe àgbéyẹ̀wò yii nipa Nollywood.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni ó tún ń ṣe àgbéyẹ̀wò ètò orí amóhùnmáwòrán àti ipò tí wọ́n wà..Ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ rẹ̀ wọ́n dá pèpéle Nollywood Reinvented kalẹ̀ ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kíní, ọdún 2011. Wọ́n dá sílẹ̀ láti lè mú ìdàgbàsókè bá sinimá ilé Nàìjíríà tí ó wà ní orí ẹ̀rọ ayélujára, kí ó tún lè jẹ́ ìtọ́ka sí fún àwọn òǹwòran lápapọ̀.. | wikipedia | yo |
O le ni ogorun osere ile Naijiria ati osere ile Ghana ti pèpéle yi ti ṣàgbéyẹ̀wò gege bi osere. Pèpéle yi wa gege bi Atọ́ka nipa tso ati ipo awon osere ati sinima won wa fun awon ololufe won, siso ipo yi naa tun da lori ise lámèyítọ́ nipa bi awon ololufe ere sinima Nollywood se n kopa ninu siso ipo ti osere kan tabi òmíràn, sinima kan tabi òmíràn wa lori ayelujara.. | wikipedia | yo |
yínyan àwọn olùkópa sábà ma ń wáyé ní ìbẹ̀rẹ̀ oṣù Karùún tàbí ìkẹfà tí ó sì jẹ́ wípé àwọn òǹwòran ni yóò yan àwọn ènìyàn tàbí fíìmù tí yóò kópa nínú ayẹyẹ àmì náà tí ètò ìdìbò yí yóò sì tó oṣù mẹ́ta gbáko kí ó tó kásẹ̀ nílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí ni wọ́n yóó kéde àwọn tí yóò kópa ní oṣù Kejìlá ọdún.Ẹ tún lè wo rating site YNaija àwakẹ́ningàwọn ìtọ́ka síàwọn ìjásóde Official website.. | wikipedia | yo |
Unun Women and Others Àwọn obìnrin ti kọ́ wọ́pọ̀ ati àwọn yoku (ọdún 1977), jẹ́ eré àkọ́kọ́ ti gbajúgbajà onọn-eré-orí ìtàgé ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà ní Sengle Ogun, Wendy Wassers | wikipedia | yo |
Igi oṣè jẹ́ igi tí ó wọ́pọ̀ láàárín àwọn elédè Yorùbá ní ìpínlẹ̀ Kwara.Àwọn ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀ka Ètò Ìdájọ́ Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ́ ọ̀kan nínú ẹ̀ka mẹ́ta ti Ìjọba Ìpínlẹ̀ Èkó tí ó wà lábẹ́ Ìwé Òfin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti òfin ti Ìjọba ti Ìpínlẹ̀ Èkó.Àwọn Ìtọ́kasí.. | wikipedia | yo |
October Rain jẹ́ ayẹyẹ tó ma ń wáyé lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo lọ́dún.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ àkójọpọ̀ ẹgbẹ́ àwọn oníṣẹ́ ọnà ilé Nàjíríà, ìyẹn ‘Society of Nigerian artits (San).. | wikipedia | yo |
Àsìkò ayẹyẹ àjọ̀dún yìí ni ọ̀pọ̀ nínú àwọn oníṣẹ́ ọnà náà ma ń ṣàfihàn iṣẹ́ ọnà àtinúdá wọn fáráyé rí, àti láti le ṣègbélárugẹ fún àwọn ènìyàn tí ó ti tiraka láti kópa nínú ìdàgbà-sókè orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Julie Marie Benz ( ojo ibi ojo kini osu karun ,1972) osere birin ile Amerika, ti a mo si darla ninu Buffy the Vamire Sikùn ati Angel (1997-2004) ati Rita Bennett ninu Dexter (2006–2010), ninu eyi ti o ti gba ami eye Satẹlaiti fun osere birin ti oni ifowoṣòpò ni odun 2006 ati ami eye tun ni 2009.. | wikipedia | yo |