cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ìpele méje ni omi-iṣan-orókè yìí ní, lórí rẹ̀ ni abúlé Abake waomi-iṣan-orókè erin-Ìjẹ̀ṣà yìí jẹ́ ìrìnàjò afẹ́ tó gbajúmọ̀ fún àwọn ilé-ẹ̀kọ́ ní agbègbè náà..
wikipedia
yo
Àwọn aráàlú ká omi-iṣan-orókè yìí gẹ́gẹ́ bíi ààyè àbòwó àti ọ̀nà ìsàfọmọ ẹ̀mí..
wikipedia
yo
Wọ́n má ń ṣe ọdún ìbílẹ̀, àti ẹ̀là ṣiṣẹ́ ní ààyé yìí tẹ́lẹ̀.Wo eléyìí náà àkójọ tí àwọn ìṣun omi lọ́gosí warm Springsí ìwé Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ṣíṣe ìwòsàn àlébù tí ó lè fa ìpèníjà jẹ́ ojúṣe akọ́ṣẹ́ elétò ìlera.
wikipedia
yo
Nínú ìmọ̀ ìṣirò owó, ó jẹmọ́ ìdíyekù tí ó máa ń dé bá dúkìá ìṣòwò tí ó ti pẹ́ nílẹ̀.
wikipedia
yo
Clet water act ó jẹ́ Tápà láàárín omi tó dà geere àti èyí tí kò dá geere..
wikipedia
yo
Tiwatope Savage-Balogun (Bii ni ojo karun, osu keji, odun 1980), ti awon eniyan mo si Tiwa Savage, je akọrin, oluṣakoso orin, onise ati oṣere ilu Naijiria..
wikipedia
yo
Lọ́wọ́lọ́wọ́, o ní ìsọ̀wọ́ Ṣíṣàkóso-orin pẹ̀lú Sony/Atv Music Publishing..
wikipedia
yo
Savage fi owó sí àdéhùn ìṣe pẹ̀lú Gvin Records ní ọdún 2012, ó tún fi ọwọ́ sí àdéhùn ìṣàkóso pẹ̀lú Roc Nation ní oṣù kẹfà, ọdún 2016 tí ó jẹ́risí ní orí Instagram..
wikipedia
yo
O pẹlu awọn miran lati kọ orin Colard Greens & Cornbread lati inu Alibọ́ọ̀mù ti wọn yan fun ẹyẹ Grammy, Back to Me..
wikipedia
yo
Tiwa Savage ṣe àfíhàn lórí Solar Ọ̀dọ́v, Àkójọ Alibọ́ọ̀mù ti Mavin Records ṣe afihan rẹ̀..
wikipedia
yo
álíbọ́ọ̀mù àkọ́kọ́ rẹ̀, once upon a time, jáde ní ọjọ́ kẹta, oṣù keje, ọdún 2013..
wikipedia
yo
Savage jẹ́ ẹni tí ó ma ń kọ orin ní èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Yorùbá..
wikipedia
yo
Awon ebi re ko lo si ilu lonodenu nigba ti o wa ni omo odun mokanla..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wà ní ilé-ìwé gíga, ó jẹ́ ẹni tí ó ma ń fún trombone fún Orchestra band ilé-ìwé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó dàgbà sí inú ètò ọ̀pọ̀lọpọ̀ àṣà látara lọdì rẹ̀ láti Nàìjíríà lọ sí United Kingdom àti láti United Kingdom lọ sí United States..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó jáde pẹ̀lú iyì nínú Business Administration láti University of Kent, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní ma ṣiṣẹ́ ní The Royal Bank of Scotland..
wikipedia
yo
O ṣe ẹlẹgbẹ fun George Michael nigba ti o wa ni ọmọ ọdun merindinlogun ati fun Mary J..
wikipedia
yo
Bblige, Chaka Khan, Blu cantrell, Emma Bunton, Kelly Clarkson, Andrea Bohop ati ms..
wikipedia
yo
O ti ṣere lori itage pẹlu sting, 50 cent, the Black eyed peas, Eminem, Robbie Williams ati Destiny's Child lati mẹ́nu ba die.Savage fi orúkọ sílẹ̀ ní Berklẹ́ẹ̀ College of Music ó sì jáde pẹ̀lú iyi nínú Ọ̀jọ̀gbọ́n orin ní ọmọ ọdún mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ń níní àwọn ìrírí rẹ̀ níbẹ̀, oní òun rí ìwúrí látara ìfẹ́ àwọn Odò akẹ́kọ níbẹ̀ àti wípé òun nílò agbèègbè iléwe na..
wikipedia
yo
Savage sọ̀rọ̀ ránpẹ́ lórí àwọn ìpèníjà tí àwọn akọrin ma ń dojúkọ tí wọ́n báfẹ́ yí sí adarí orin láti ẹlẹgbẹ́ àti wípé wọ́n ma ń dojúkọ ìyẹ̀wò nígbà tí eré wọn ò bá jẹ́ ǹkankan..
wikipedia
yo
Owó rẹ ràn lọ́wọ́ láti mọ̀ nípa ilé-iṣẹ́ orin Nàìjíríà dópin..
wikipedia
yo
Savage sọ̀rọ̀ nípa owó rẹ̀ àti pé ìpele ọ̀jọ̀gbọ́n rẹ̀ kò jẹ́ kí ó ní ìfarahàn sí ẹ̀tàn.Ní ọdún 2016, Savage kópa nínú UK Edition ti the x factor tí ó ṣi lọṣíwájú láti wà lára àwọn mẹ́rìnlélógún tí ó gbẹ̀yìn nígbà tí ó ń lo ilé-ìwé tí a mẹ́nu bà lẹ́ẹ̀kan..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ń kópa nínú ìyẹré na, ó kojú àwọn ìṣòro kan.Ní ọdún 2009, Sony/at Music Publishing Bulu Savage fún iṣẹ́ orin kan tí ó fún ní agbára láti kọ orin fún Babyface, Kat del-Eta, fanta Barrino, Monica àti Mya..
wikipedia
yo
Bákannáà, ìbáṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú Fantasia lórí Orin "Colard Greens & Cornbread" jẹ́ kí ará Amẹ́ríkà nã gba yíyan fún ẹ̀yẹ Grammy ní ọdún 2010..
wikipedia
yo
Savage kọ orin jáìco "oh Yeah" tí ó ṣàfihàn snoop dog pẹ̀lú orin Kat delùná "Push Push" tí ó ṣàfihàn Akon àti David GuEtta..
wikipedia
yo
Bi o ṣe nifẹ si ki o ma kọ orin fun awọn akọrin yoku to, o nifẹ si ki o ma kọ orin fun ara rẹ julọ..
wikipedia
yo
Bakanna, o se fiimu akọkọ rẹ pẹlu Joke Silva ati Ireti Doyle ninu ere ori-itage for Coloured Girls..
wikipedia
yo
Savage jẹ́ ará-ìlú Áfíríkà àkọ́kọ́ lóbìrin tí ó níṣẹ́ pẹ̀lú ẹ̀yà Pepsi lẹ́yìn tí ó bu owó lu ìwé pẹ̀lú wọn.Ọdún 2010 títí di 2013; "Once Upon a Time", Iṣowo Mavin Records, Iṣẹ Ọmọnìyàn ati Ìfọwọ́síwe Ṣẹ̀dásilẹ Lebélì rẹ̀, 323 Entertainment, pẹlu Olùṣàkóso ati ọkọ rẹ̀ igbana Tunji "Tẹ́ẹ Bills" Balogun ti o ṣàdéhùn igbeyawo fun ni ojo karun, oṣu keji, ọdun 2013..
wikipedia
yo
Ó darapọ̀ mọ́ Mavin Records tí Don Jazzy ní ọdún 2012..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn akọrin tó darí lórí Solar Ọ̀dọ́vus, Alibọ́ọ̀mù tí Kumas náà ṣe àkójọpọ̀ rẹ̀ ní 2012..
wikipedia
yo
Savage bẹ̀rẹ̀ sí ní ma gba álíbọ́ọ̀mù akọkọ rẹ silẹ ni ọdun 2010..
wikipedia
yo
O Netiki pẹlu awọn alumini Berklée bii Keith Harris, Derek pàtẹ, Scott Coleman, radar Ellis ati darien Dorsey nigba ti o fi n lo ile-iwe na..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú Brenda píke, ó ní òún ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn asàgbéjáde orin bíi Amúṣan Harmony, Warren “oak” àpáwà àti So Sick (Da Grin) láàrín àwọn yòókù..
wikipedia
yo
Bakanna, o so wipe Alibọ́ọ̀mù akoko re yoo ni orin ni ede abínibii re..
wikipedia
yo
Savage ṣe àfihàn lórí "òyí nígbàkigbà" tí flaour n'abania ní ọdún 2012..
wikipedia
yo
Síwájú kí ó tó ṣiṣẹ́ papọ̀ pẹ̀lú flavour, ó ṣe ẹ̀yà orin ná.Láti kópa nínú àjọyọ̀ ọdún méjìléláàdọ́ta ti Nàìjíríà gba òmìnira, Savage ṣe ìjábọ̀ “Arise, O Com."[ots” fún Ndani Ses..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kannlá, Ọdún 2012, Savage ṣiṣẹ́ papọ̀ pẹ̀lú wájẹ́, Pizto, Tiran Dœrin àti Pamela Geke lórí àkòrí-orin Ovation Red Carol “Higher
wikipedia
yo
Ni Oṣu Karun, ọdun 2013, Savage pe patì lori títẹ́tí si Alibọ́ọ̀mù ni The WWat Baker Hotel ni Ikoyi..
wikipedia
yo
O ṣafihan gbogbo orin to wa lori álíbọ́ọ̀mù na o si kede iceberg Slim, Sarkodie ati General Pype gẹgẹbi awọn ti wọn kopa..
wikipedia
yo
Ní ọjọ́ kẹta, oṣù keje, ó ṣe àfihàn álíbọ́ọ̀mù rẹ̀ àkọ́kọ́, once upon a time, fún gbogbo àwọn ọmọ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Alibọ́ọ̀mù na jáde lórí ìroye ni òkú ọ̀la kí o jàre ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Savage So Alibọ́ọ̀mù na ni once Upon a time lati ṣafihan awọn ohun rere ti o ṣẹlẹ ninu igbesi aye rẹ..
wikipedia
yo
O sọ wipe oun fe je iwuri fun awon olorin to mbọ lona wipe, igba kan ri o, oun je ọmọbirin kekere lati isalẹ Eko ti o ni lọkan lati di irawọ..
wikipedia
yo
Alibọ́ọ̀mù na pelu awon orin oselu bii "Middle Passa", ti o so nipa Itíràka awon omo Afirika ni ilu ajeji.Savage ti kopa ninu ọpọlọpọ iro odo lagbara ati eto ayewo ọmú awon obirin fun Alákàn kakiri Naijiria..
wikipedia
yo
Savage ti ṣe iranlọwọ lati gbe ọwọ jade fun awọn ile-iṣẹ ti o n kọ ile-iwe ni ilu rẹ..
wikipedia
yo
Ní oṣù keje, ọdún 2013, ó fọwọ́ sí àdéhùn pẹ̀lú MTN Nàìjíríà tí ó ń lọ sí ọgbọ̀n mílíọ̀nù Nera..
wikipedia
yo
O tun fọwọsiwe iṣe pẹlu Pepsi, Forte Oil ati Maggi.awọn ipenija ti o dojukọ ni ile-iṣẹ orin Naijirianigba ti Savage te papa orin Naijiria, ko mọ ọ un ti oye ki o reti..
wikipedia
yo
Bakanna, o gba opolopo ìpayà ati ìkanra lowo awon ti won lero wipe kole yege..
wikipedia
yo
O sọ wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni ó gbìyànjú àti yí ọkàn rẹ padà nípa títẹ̀dò sí Nàìjíríà rẹ̀..
wikipedia
yo
Bakanna, awon eniyan so fun wipe won o le gba wole gegebi akorin obinrin..
wikipedia
yo
Ni itesiwaju, won so fun wipe ko le lo ori itage kanna pelu awon bii tuface ati Wizkid..
wikipedia
yo
Savage ò jẹ́ kí àwọn ọ̀rọ̀ òdì nà yílọ́kàn padà nípa ṣíṣe iṣẹ́ orin..
wikipedia
yo
Orin na, ti o ni ohun retiro R&B ati Funk jẹ agbejade lati owo spell..
wikipedia
yo
Savage kópa lórí orin-ẹlẹ́yọkan tí rèékado Banks "Turn It Up" tí ó jẹ́ àgbéjáde láti ọwọ́ Don Jazzy..
wikipedia
yo
Ni ojo kini, osu karun, odun 2014, Mavin se agbekale "KOATOto" ti Savage, Don Jazzy, Dr Sid, D'Prince, rèéka Banks, Fabode Bello ati di'ja kopa ninue..
wikipedia
yo
Orin yi, ti o je agbekale lati owo Don Jazzy, je akoko ajose ti Lebélì na gbe jade lati igba ti won ti se agbejade Alibọ́ọ̀mù Solar abẹrẹus ni odun 2012.Ni ojo kokandinlogun, osu karun, odun 2014, Foirun Sitank fi "gírd ‘O' bonb" ti Patoranking ti Savage ṣafihan lori e ṣaaju, orin na je agbekale lati owo Wi8..
wikipedia
yo
Wọ́n ya fídíò orin ná ní Lọndọnu tí láìjẹ́ Musa sì ṣe ìtọ́sọ́nà rẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n gbé sí orí vevo àkáǹtì Patoranking ní ogúnjọ́, oṣù karun, ọdún 2014 tí gbogbo gígùn rẹ̀ sì jẹ́ ìṣẹ́jú mẹrin àti àáyá méje..
wikipedia
yo
Ni ojo keje, osu kefa, odun 2014, Savage kopa ninu MTV Africa Music Awards ti odun 2014 pelu Miguel, flaour N'abania, Davido, !kiz. UHuruh, Ooski ati professor..
wikipedia
yo
Ni ojo ketadinlogbon, osu karun, odun 2014, 323 entertainment ati Gvin Records se agbekale fidio "wanted" ti o je orin lati inu Alibọ́ọ̀mù once upon a time..
wikipedia
yo
gbárabu Musa ni o ṣe itọsọna fidio na ni Lọndọnu.Ni osu kefa, ọdun 2014, Savage sise papo pelu mi Casa, lola hop, Sarkodie, diamond Playemi ati Davido lori orin kan fun ipolongo Africa Rising ti DSTV ti won se lati le jẹ iwuri fun awon omo Afirika lati kopa ninu awọn iṣẹ akanṣe lori yínkọ́wọ́ ti o wa láwùjọ..
wikipedia
yo
Fídíò orin na, ti o jade ni ojo kẹrinlelogun, osu kefa, odun 2014, je didari ati gbigbekale latọwọ ile-iṣẹ South Africa kan, callback Dream..
wikipedia
yo
Àwọn akọrin na kọ orin na níbi ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀ Africa Rising ni Mauritius..
wikipedia
yo
Ni osu kefa, odun 2016, awuyewuye wa laarin awon to n gbe iroyin jade wipe Savage ti fi owo si iwe ise isakoso pelu Roc Nation..
wikipedia
yo
Ni ojo kokandinlogbon, osu keje, odun 2016, o fidi oro na mule nipa ọrunwo re látara àkáǹtì re lori Instagram eleyi si se ni omo Naijiria akoko ti o ma wa lori lebélì na.igbesi ayerisi fe Tunji "Tẹ́ẹ Billz" Balogun ri..
wikipedia
yo
Ni ojo ketalelogun, Oṣu kọkanla, ọdun 2013, tọkọtaya na ṣe igbeyawo ibile wọn ni The Ark ni Lekki..
wikipedia
yo
Igbeyawo alaṣọ funfun na waye ni ojo kerindinlogbon, osu kerin, odun 2014 ni Armani Hotels ni Dubai..
wikipedia
yo
Ni ojo kini, osu kini, odun 2015, Savage ati oko re kede wipe awon n reti akobi won..
wikipedia
yo
Ni ojo kejilelogun, osu keje, odun 2015, Savage bi ọmọkunrin ti won so ni JaMil Balogun..
wikipedia
yo
Ni ojo kejidinlogbon, osu kerin, odun 2016, "Tẹ́ẹ Billz" Balogun, ninu ọpọlọpọ ifiránṣẹ́ lori Social Media, fi esun agbere kan iyawo re o si fi esun aje kan iyare..
wikipedia
yo
Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò oníṣẹ́ju marundinlaadọta tí ìwéròyìn ThisDay àti Pulse Nigeria ṣe, tíwá Savage kókọ́ gbogbo òun tí ọkọ rẹ̀ sọ lórí Social Media ní kíkún..
wikipedia
yo
O dábàjẹ́ ẹ̀sùn àgbèrè tí ọkọ rẹ fi kàn ọ́ sì fi ẹ̀sùn iná àpà, ìnífẹ̀sódì ogún ọlọ́rọ̀ àti ipátì..
wikipedia
yo
Bakanna, o so wipe igbeyawo oun pelu re ti DÓPIN.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Tiwatope Savage-Balogun (tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún Oṣù Kejì ọdún 1980), tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí Tiwa Savage, jẹ́ akọrin, olùṣàkóso orin, oníṣẹ́ àti òsèré ìlú Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó fọwọ́ síwèé pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ òǹtẹ̀wé kan Sony/Atv Music Publishing..
wikipedia
yo
Savage fi ọwọ́ síwèé iṣẹ́ pẹ̀lú Gvin Records ní ọdún 2012, ó tún fi ọwọ́ síwèé pẹ̀lú Roc Nation ní oṣù kẹfà, ọdún 2016 tí ó sì jẹ́rĩisi ní orí Instagram..
wikipedia
yo
Ó pẹ̀lú àwọn mìíràn láti kọ orin Collard Greens & Cornbread láti inú album tí wọ́n yàn fún àmì ẹ̀yẹ Grammy, Back to Me..
wikipedia
yo
Tiwa Savage ṣe àfíhàn lórí Solar Ọ̀dọ́time, Àkójọ Album ti Mavin Records ṣe àfihàn rẹ̀..
wikipedia
yo
Album àkọ́kọ́ rẹ̀, Once Upon a time, jáde ní ọjọ́ kẹta, Oṣù Keje, Ọdún 2013..
wikipedia
yo
Savage jẹ́ ẹni tí ó máa ń kọ orin ní èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Yorùbá..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó wà ní ilé-ìwé gíga, ó jẹ́ ẹni tí ó maa ń fún trombone fún Orchestra band ilé-ìwé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ó dàgbà sínú ètò, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àṣà látàrí lọlọ rẹ̀ láti Nàìjíríà lọ sí United Kingdom àti láti United Kingdom lọ sí United States..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó jáde pẹ̀lú iyì nínú Business Administration láti University of Kent, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní máa ṣiṣẹ́ ní The Royal Bank of Scotland..
wikipedia
yo
O ti ṣere lori itage pẹlu sting, 50 cent, the Black eyed peas, eminem, Robbie Williams ati Destiny's Child lati mẹ́nu ba die.Savage fi orúkọ sílẹ̀ ní Berklẹ́ẹ̀ College of Music ó sì gboyè nínú Music..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ń ṣàtúnyẹ̀wò àwọn ìrírí rẹ̀, ó sọ ọ́ di mímọ̀ pé ìwúrí òun wà látàrí ìfẹ́ tí àwọn ọ̀dọ́ akẹ́kọ̀ọ́ fi máa ń hàn sí ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí..
wikipedia
yo
Savage sọ̀rọ̀ ránpẹ́ lórí àwọn ìpèníjà tí àwọn akọrin máa ń dojú kọ tí wọ́n bá fẹ́ yí sí adarí orin láti ẹlẹgbẹ́ àti wípé wọ́n máa ń dojú kọ ìyẹ̀wò nígbà tí eré wọn ò bá jẹ́ nǹkankan..
wikipedia
yo
Ó tún sọ̀rọ̀ nípa ọwọ́ rẹ̀ àti pé ìpele ọ̀jọ̀gbọ́n rẹ̀ kò jẹ́ kí ó ní ìfarahàn sí ẹ̀tàn.Ní ọdún 2016, Savage kópa nínú UK Edition ti the x factor tí ó ṣi lọṣíwájú láti wà lára àwọn mẹ́rìnlélógún tí ó gbẹ̀yìn nígbà tí ó ń lo ilé-ìwé tí a mẹ́nu bà lẹ́ẹ̀kan..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò pẹ̀lú Brenda píke, ó ní òún ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn asàgbéjáde orin bíi Amúṣan Harmony, Warren “Oak” àpáwà àti So Sick (Da Grin) láàrín àwọn yòókù..
wikipedia
yo
Savage ṣe àfihàn lórí "òyí kalẹ̀b" tí flaour n'abania ní ọdún 2012..
wikipedia
yo
O sọ wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni ó gbìyànjú àti yí ọkàn rẹ̀ padà nípa tíTẸ̀TẸ̀ sí Nàìjíríà rẹ̀..
wikipedia
yo
Ni ojo kokandinlogbon, osu keje, odun 2016, o fidi oro na mule nipa ọrunwo re látara àkáǹtì re lori Instagram eleyi si se ni omo Naijiria akoko ti o ma wa lori lebélì na.igbesi ayeSavage fe Tunji "Tẹ́ẹ Billz" Balogun ri..
wikipedia
yo
Nínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò oníṣẹ́ju marundinlaadọta tí ìwéròyìn ThisDay àti Pulse Nigeria ṣe, tíwá Savage kókọ́ gbogbo òun tí ọkọ rẹ̀ sọ lórí Social Media ní kún..
wikipedia
yo
O dábàjẹ́ ẹ̀sùn àgbèrè tí ọkọ rẹ fi kàn ọ́ sì fi ẹ̀sùn iná àpà, ìnífẹ̀sódì ogún ọlọ́rọ̀ àti ipá..
wikipedia
yo
Ọ̀rọ̀ wà nínú àwọn àjọ̀dún ńlá ti àwọn Yorùbá ma ń ṣe ní ọdọọdún..
wikipedia
yo
Ọdún Oro jẹ́ Oókan Pataki ninu Ọdún tí Àwọn Ẹ̀yà Yorùbá ma ń ṣe..
wikipedia
yo
Ọ̀sà nlá gidi gan ni ọ̀rọ̀ jẹ́, wọ́n a sì ma bòó ní ọdọọdún..
wikipedia
yo
ọ̀rọ̀ jẹ́ ọré kan tó ṣépè ọmọ ọkùnrin nìkan ló lè fojú rí tó sì lé bòó pàápàá jùlo lọ́dọ̀ àwọn tí àjọ̀dún yíi bá tan mọ́..
wikipedia
yo
A kì wo ni ọrọ̀ fún ẹni tí kò bá ń ṣe ọmọ ọlọ́rọ̀ pẹ̀lú fún obìnrin lápápo..
wikipedia
yo