cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
O kò pa nínú Roswell series (1999-2000), Desperate Housewives (2010), ( Kò sí ẹbí lasan)No Ditary Family (2010–2011), (Okunrin to le bun) The gifted Man (2011-2012), (2013–2015),2015), and Hawaii Five-0 (2015-present)..
wikipedia
yo
Awon ebi re tedo si eba Murrysville nigbati Benz je omo odun meji, and she started ice skating when oun se ayarabi asa lori yin yin ni omo odun meta..
wikipedia
yo
O se ifiga gbàga nii1988 us osi kẹ́sẹ járí; ni pa eko giga ipele ninu ijo jíjó lori yinyin pelu eni keji re ti amo si, David Schilling, ti won si pari si ipo ketala.tii nigba Benz pe omo odun merinla, o kan lese otun ti ko je ki ole ko pa mo.References awon Ọjọ́ìbí ni 1972 alààyè.. Ogun Ogun
wikipedia
yo
New Money (Owó Tuntun) jẹ́ eré ìtàgé Δriin tí a gbé jáde ní ọdún 2018 ní orile-ede Naijiria Tope Oshin ni oludari ere náà nígbà ilé iṣẹ́ Inkblot Productions àti FilmOne gbé ẹ jáde fíímù na sọ ìtàn ọmọ kan tí ó ń bá ní ta'jà tí ó ní ìròngbá lati di àṣọ́ tí ó wa máa wá rí ìpín tire gba nínú ogún bàbá rẹ̀ ti o ti fi gba igba' gba' ní ọdún kúrò ní ọdún rẹ̀ (owo ní ó ti gbà ni ó ti kọ́ ní o wa ni ọdún rẹ̀ ni ọdún rẹ̀ ni ọdún rẹ̀ ti o ti fi agbo rẹ̀ ní ó gbé jáde ní ọdún rẹ̀ ni agbo rẹ̀ tí ó ti o wa ti o gbe ni ọdún rẹ̀ ni ó máa ń di ni ó wá maa gba ìpín rẹ̀ * gbogbo ni olú kan * ti o ti fi maa fi ọdún kan ti ọdún rẹ̀ ni ọdún rẹ̀ lati ọdún rẹ̀ ti o ti fi ipin ilé rẹ̀ ní ipin rẹ̀ ti pa ọmọ ti fi ti ọdún rẹ̀ ní ọdún rẹ̀ ni ó maa agba — ] jẹ́ ìjò tí ó ti o wá tí o wa ti a gbe jáde tí ọdún rẹ̀ ti o ti fi ìfi kan ni gi ní agbo rẹ̀ ti kan ti o kan ti o kan ti o ti ta ni ó ní ọdún kan lati
wikipedia
yo
Inkblot àti FilmOne tún pa'wọ́ pọ̀ ṣe fiimu lẹ́ẹ̀kan sí lẹ́yìn tí wọ́n ṣe fiimu The Wedding Party 2.àgbékalẹ̀ eré New Money (owó tuntun) sọ ìtàn ọmọ ọdún mẹ́tà-lé-lógún kan ti a n pe orúkọ rẹ̀ ní tòun (Jemima Osunde), ti o ṣ'ade ba ara rẹ ni aarin gbùngbùn ọrọ̀ nigbati baba rẹ (Kalu Ikeagwu) fi ilé iṣẹ́ rẹ ti o níye lórí tó ọ̀pọ̀lọpọ̀ bilionu sílẹ̀ fun un nínú ìwé ìpíngún rẹ̀..
wikipedia
yo
Ipinnu rẹ yii sọ ile ise na sinu ọpọlọpọ iṣoro, eleyi ti o si mu ki awon eniyan ri Toun gege bi oludari ti ko kun oju oṣuwọn.Awon osere ti o ko'pa nibẹ Jemima Osunde gege bi Toun Odumo Kate Henshaw gege bi Fatima Dakore Akande gege bi Ebube Wale Ojo gege bi Chuka Wofáì Afara gege bi Binta Adeolu Adefarasin gege bi Patrick Daniel Etim Aláwọ̀ong gege bi Ganiyu o deSass Igho gege bi Angela Blossom 10th gege bi Joseph Falz gege bi Quam Kalu Ikeagwu gege bi Ifeanyi Femi branch Bikiya Graham-Douglas Rita Edwards gege bi mọ́níjà Yolanda Okereke ni Tiata a gbe fiimu yi jade fun igba akoko ni ile sinima Ix ti o wa ni adugbo lẹ́kì lẹ́kì, ni ilu Eko lati owo awon ile ise meji ti o ngbe ere jade ere jade, Inkblot ati FilmOne ni osu keta keta-le-logun osu keta odun 2018. With unre. with Kági itọ si..
wikipedia
yo
Aapala jẹ́ ẹ̀yà orin, tí a múwá láti ọ̀dọ̀ àwọn .Yorùbá ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ èyí tí ó gùn lé Sítáì pákósan tí ó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ ní òpin ọdún 1930 lọ sókè, ní ìgbà tí wọ́n ń lò ó láti jí àwọn olùsìn lẹ́yìn ààwẹ̀ lásìkò oṣù mímọ́ lámuana ti àwọn ìmọ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ìmìtìtì àpàlà gbòòrò sí pẹ̀lú àsìkò, ó fi orin kúbáni ṣe àtẹ̀gùn tí ó sì di gbajú-gbajú ní Kánádà..
wikipedia
yo
Àwọn mìíràn lè lòdì sí èyí pé àyìnlá Ọmọra ni wọ́n mọ̀ jù, tí ó sì jẹ́ olórin àpàlà tí ó ṣoríire jùlọ..
wikipedia
yo
Àwọn méjèèjì ni ó kó ipa mọ́yàmi nínú mímú ẹ̀yà orin yìí di ìlúmọ̀ọ́ká, ó sì yàtọ̀ sí, ó dàgbà jù, ó sì nira kàkà láti mọ̀ ju Fújì lọ..
wikipedia
yo
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àyìnlá Ọmọgbọ̀n kú nígbà tí ó wà ní ọmọ ogójì ọdún ó lé díẹ̀ ní ọdún 1980..
wikipedia
yo
Ó ṣe àwo tí ó ju ogún lọ, tí ó sì jẹ́ pé gbkogbọ́ wọn ni ó ṣe ní àṣeyọríbí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Fuji ṣì dúró gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà orin ìbílẹ̀ tí ó ṣe pàtàkì jùlọ láàrín àwọn Yorùbá ní Nàìjíríà, apálà sì gbajúmọ̀ dáadáa láàrín àwọn ẹ̀yà Yorùbá tí ó jẹ́ ilàmùsùlùmí]] 🙂
wikipedia
yo
Ọ̀nà ọ̀tọ̀ ni a ti gbọ́dọ̀ máa dárúkọ ọmọ Haruna Ìṣọ̀lá, músílíù Haruna ìṣọ̀lá ẹni tí wọ́n ń gbóríyìn fún nípa mímú àpàlà kúrò nípò òkú, tí ó sì nìkan ṣe agbátẹrù àjíǹde àpàlà ti ọdún 2000pẹ̀lú àwo orin rẹ̀ ti ọdún 2000 (tí ó pè ní ‘sóyòyò) músílíù tí ṣe àṣeyọrí nípa mímú kí orin àpàlà fẹjú síi, sí etíìgbọ́ àwọn ọ̀dọ́, ó ṣe bẹ́ẹ̀ mi èémí ọ̀tún sí inú ẹ̀yà orin yìí bẹ́ẹ̀ náà ni ó mú àṣà (iṣẹ́ takuntakun bàbá rẹ̀) wà láàyè..
wikipedia
yo
Ó gba oríyìn mímú ẹ̀yà orin yìí gbajúmọ̀ padà èyí tí ó ti n di ti àwọn mùsùlùmí ẹ̀yà Yorùbá ayé àtijọ́..
wikipedia
yo
Àṣeyọrí àwo orin ‘sóyòyò túmọ̀ pé ọ̀dọ́ (lọ́pọ̀ ìgbà onígbàgbọ́ tàbí abọgibọ̀pẹ̀) òde òní tí Yorùbá ti wá ń ṣàfihàn ìfẹ́ wọn nínú orin àpàlà..
wikipedia
yo
A lè gbọ́ orin rẹ lọ́pọ̀ ìgbà ní ilé iṣẹ́ ẹ̀rọ asọ̀rọ̀mágbèsi káàkiri ilẹ̀ Yorùbá.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Ọdún ogún jẹ́ ayẹyẹ ọdọọdún ti àwọn ènìyàn Yorùbá ìpínlẹ̀ Oǹdó, Nàìjíríà máa ń ṣe fún bíbú iyì fún ogun, jagunjagun àti irúnmọlẹ̀ oníṣẹ́ irin tí àwọn Yorùbá gbà pé òun ni òrìṣà tí ó kọ́kọ́ de ilẹ̀ ayé.Ìtàn rẹ̀gẹ́gẹ́ bíi ìgbàgbọ́ àwọn Yorùbá, ogún jẹ́ ọba ó sì jẹ́ baba Ọ̀rànmíyàn òun sì tún ni ènìyàn àkọ́kọ́ láti dé sí ilé ayé; ó ṣàmúlò àdá àti ajá láti yẹ ọ̀nà fún àwọn irúnmọlẹ̀ yòókù láti kọjá..
wikipedia
yo
Òun ni wọ́n tún sọ pé ó ṣe ìkádìí iṣẹ́ lára àwọn ènìyàn àkọ́kọ́ tí Ọbàtálá dá, òòṣà Aṣẹ̀dá àwọn Yorùbá..
wikipedia
yo
Ọdún rẹ̀ máa ń ṣáábà wáyé láàrín oṣù kẹjọ tàbí oṣù kẹsàn-án ní ìpínlẹ̀ Òndó àti àwọn apá ibìkan ní ìpínlẹ̀ Èkìtììpalẹ̀mọ́ rẹ̀ìpalẹ̀mọ́ fún ayẹyẹ ọdún bẹ̀rẹ̀ láti ó kú ìtàdógún, àwòrò ogun yóò kéde rírí oṣù tuntun (èyí tí wọ́n gbọdọ̀ rí kí wọ́n tó lè bẹ̀rẹ̀ ọdún) nípa fífọ́n Lárù (fèrè ìbílẹ̀) fún ọjọ́ méje..
wikipedia
yo
Ọjọ́ kẹsàn-án lẹ́yìn tí wọ́n ti rí oṣù tuntun, ọba yóò rán ikọ̀ lọ láti lọ kéde ayẹyẹ ọdún..
wikipedia
yo
Lára ìpalẹ̀mọ́ fún ọdún ni títún afárá ṣe àti yíyẹ̀ ọ̀nà..
wikipedia
yo
Ọdún ń tẹ̀ síwájú pẹ̀lú àìsùn ilágun, aṣóró tàbí àìsùn ogún tí ó máa ń wáyé ní ọjọ́ ogún ku ọ̀túnla..
wikipedia
yo
Àwọn alágbẹ̀dẹ ìlú Ifẹ̀ yóo kó àdá tuntun, ọkọ́ ati ṣaworo wá, wọn ó sì fi ẹfọ̀n, owó ẹyọ ati àwọn nǹkan mìíràn ṣe ẹwà sí ojúbọ..
wikipedia
yo
Wọn a ta ọtí sí òòṣà, wọ́n á jó yíká ojúbọ wọn a sì wúun..
wikipedia
yo
Wọn a pèsè ajá fún ìrúbọ.Ọdún ga-ánọjọ́ mẹ́ta tí ó gbẹ̀yìn ọdún yìí máa ń lágbára..
wikipedia
yo
Àkọ́kọ́ nínú ọjọ́ yìí ni wọ́n á pa ajá tí ó jẹ́ kókó ọdún náà..
wikipedia
yo
Ènìyàn méjì yóò fa ajá náà bí ẹni pé wọ́n ń fà á mọ́ ara wọn lọ́wọ́ wọn a jẹ́ kí ẹ̀mí rẹ̀ máa lọ díẹ̀díẹ̀ pẹ̀lú ìnira.Ìgbà míràn àwòrò ogun yóò fi àdá bẹ́ ajá yìí kí ó tó kú fúnra rẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n á po ẹ̀jẹ̀ ajá yìí pọ̀ pẹ̀lú iyọ̀, orógbó, ẹmu àti epo pupa wọ́n á dàá sí orí irinṣẹ́ àwọn olùsìn rẹ̀ èyí tí wọ́n ti kó sínú abọ́ kan; wọ́n gbàgbọ́ pé èyí kòní jẹ́ kí wọ́n rí ìyọnu tí yóò sì tún mú wọn jẹ èrè tabua..
wikipedia
yo
Ogun ni baba àwọn tí wọ́n ń ṣàmúlò irin nínú iṣẹ́ òòjọ́ wọn, bíi alágbẹ̀dẹ, awakọ̀, Mẹ́kàlíìkì àti àwọn oníṣẹ́ abẹ..
wikipedia
yo
Ọdún tún lè wáyé ní ibikíbi bí ó ṣe jẹ́ pé àwòrò máa ń ṣe ọdún yìí ní Àbújá ní ìgbà míràn láìtẹ̀lé àṣẹ ìtàdógún tí wọ́n máa ń lọàwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Yéwándé Adekoya (bi ní ogunjo, Oṣù Seere, 1983), jẹ́ òṣèré, olùdarí àti olótùú eré, ọmọ orílẹ̀èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀ Ìgun-ayé àti Èkó.Ìlú ẹ̀kọ́ ni wọ́n bí Yéwándé sí ṣùgbọ́n Ọmọ Ọ̀ṣọ́-Ìjẹ̀bú ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, Ìwọ̀-Oòrùn Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O lọ si ile - eko Bright Star Nursery and Primary, ki o to tẹsiwaju fun Eko sekondiri ni Bright Comprehensive High School..
wikipedia
yo
A.) Ni Èkó Mass Communication nílé ẹ̀kọ Yunifásítì Babcock..
wikipedia
yo
Yewande Adekoya wa nile ọkọ, o si se abiyamọ.Iṣẹ sise ohun Adekoya bẹrẹ ere sise ni 2002 pelu egbe Alphabash Music and Theatre..
wikipedia
yo
O ko o si gbe ere rẹ akọkọ jade ni 2006 ti o pe ni “Life Secret”
wikipedia
yo
O ti gbe, dari, kopa ninu ọpọlọpọ fiimu Naijiria bii ọmọ ẹlẹ́mọ̀ṣọ́, Ere agbelewo 2012 kan ti o se afihan Bimbo Oshin, Muyiwa Ademola ati Yomi Fash-Lanso.won yan fiimu yin ni Ẹẹmarun ni Africa Movie Academy Awards EleKaaru..
wikipedia
yo
Wọ́n tún yàn án gẹ́gẹ́ bí “òsèrébìrin tuntun tó peregedé jùlọ” níbi ìpele Yorùbá ni City People Entertainment Award..
wikipedia
yo
Ọdún náà kanaa ni wọ́n yàn án fún ipa tí ó kó nínú kúdi Klepto gẹ́gẹ́ bíi olórí akópa òṣèrébìrin ní 2014 Best of Nollywood Awards..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Ọ̀pẹ, 2014, Adekoya gba àmì-ẹ̀yẹ fún "Disṣeyọrí jùlọ" ní Yoruba Movie Academy Awards.Fiimu rẹ Kurukuru fún ní ànfààní láti gba àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dáńtọ́ jù ní ayẹyẹ Acia 2016..
wikipedia
yo
Tope Alabi tí wọ́n tún mọ̀ sí “Oore tí ó Common” àti Agbo Jésù ni a bí í ní (Ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹwàá ọdún 1970), ó jẹ́ òṣèré, akọrin eré sinimá àti òǹkọrin Ìgbàgbọ́.Igbe ayé àti ẹ̀kọ́ rea bí Tope Alabi ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 1970 ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà fún pa Joseph Akinyele Okòródé àti Nogu Agnes Kehinde Okini..
wikipedia
yo
Oun nikan ni obinrin laarin ọmọ mẹta ninu ẹbi naa..
wikipedia
yo
Tope Alabi gba iwe ẹ̀rí ìwé mẹ́wàá (West African Examination Conncil WaEC) ní ilé ẹ̀kọ́ Ọba Akinyele Memorial High School, Ìbàdàn ní ọdún 1986..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó tẹ̀ síwájú lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gbogboǹṣe Poli Ìbàdàn (The Polytechnic Ìbàdàn) ní ibi tí ó ti kọ́ nípa ẹ̀kọ́ ìbánisọ̀rọ̀ gbogbogbòò tí ó sì jáde ní ọdún 1990..
wikipedia
yo
Tope Alabi lepa ẹkọ rẹ pẹlu ìmọ̀sílara ati ìfọkànsìn ti Eko gba.iṣẹ rẹ gẹgẹ bi òǹkọrin ati oṣeretope Alabi ti fi igba kan jẹ ọkan lara ọmọ ẹgbẹ “sters International Comedy Group"
wikipedia
yo
Ìgbà tí ó yá ó ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú àwọn ẹgbẹ́ eléré orí ìtàgé àti arinjọ ní ìlú Ìbàdàn àti Èkó..
wikipedia
yo
Alae pada di òǹkọrin igbagbọ leyin ti o di onigbagbọ tÒÔ.laarin odun 1982 si 1984 laye igba ile eko sekondiri, Ife re si orin ati ere ori itage mu un darapo mo awon ti won mo ni igba yen si "Jesters International" (Jacob, papilòlò ati Aderukò) egbe ti o wa ni Ibadan, ni ibe ni o ti ni imo ati iriri akoko ninu ere ori itage..
wikipedia
yo
O sise pelu ile ise mohunmaworan Nigerian Television Authority (NTA) Ibadan gege bii akoroyin labe abojuto ogbeni yanju Adegbitẹ, laarin odun 1990 si 1991..
wikipedia
yo
O tun sise pelu "Centre Spread advertising Limited" agbegbe ilupéjú Èkó ní odun 1991 sí 1992..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó ti ní oríṣiríṣi ìrírí iṣẹ́, Patrick Temitope Alabi padà sí iṣẹ́ eré orí ìtàgé gẹ́gẹ́ bí ó ṣe darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ olókìkí nni "Alade àròmire theartre Group" ní ọdún 1994..
wikipedia
yo
Níbẹ̀, ó ṣawari ìyàtọ̀ ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi olóore ọ̀fẹ́ àti abí òṣèré àti olórinni Alade àròmire Theartre Group wọn ṣe àfihàn agbọ̀n eré orí ìtàgé àti iṣẹ́ eré orí ìtàgé fún Tope Alabi..
wikipedia
yo
Ó kópa nínú onírunru eré àgbéléwò, eré orí ìtàgé àti pàápàá jùlọ orin inú eré gbígbé jáde èyí tí wọ́n mọ̀ ọ́n mọ̀ jùlọ tí wọ́n sì gbà gẹ́gẹ́ bí àṣẹ rẹ̀ ní ilé iṣẹ́ eré àgbéléwò Yorùbá Nàìjíríà ti ode oní..
wikipedia
yo
onírunru ònkọ̀tàn, agbéréjáde àti adarí eré ní ilé iṣẹ́ eré àgbéléwò Yorùbá ni ó ti pẹ́ Tope Alabi láti kọ àti láti gbé orin jáde fún onírunru eré àgbéléwò wọn, ó ti ní títí di oní, orin eré tí ó tó ọ̀tàdínnírínwó-ó-lé-mẹ́wàá (350) tí ó ti kọ fún oríṣiríṣi eré àgbéléwò Yorùbá..
wikipedia
yo
O ye ki a sọ nibi ti a wa yi pe Tope Alabi ní Olúlànà fún kíkọ orin Abẹ́lé ní ilé iṣẹ́ fidio àgbéléwò Yorùbá.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ọpọ́n Ifá tí wọ́n ń pè ní (La Meṣa dé Ifá ní látinni Amẹ́ríkà) jẹ́ àtẹ ìṣàyẹ̀wò nínú ìṣẹ̀ṣe Adúláwọ̀ àti ẹ̀sìn àwọn ẹ̀yà adúláwọ̀-Amẹrika, pàápàá jùlọ nínú Ifá àti ìṣẹ̀ṣe Yorùbá.Babaláwo (oniyẹ̀míwò) ṣàmúlò ọpọ́n Ifá láti le bá àwọn irúnmọlẹ̀ sọ̀rọ̀ tí wọn ó ṣàfihàn erédìí àti ojútùú sí àdáni àti ìṣòro àpapọ̀ àti mú ìdẹ̀rùn wá pẹ̀lú àwọn irúnmọlẹ̀..
wikipedia
yo
Ọpọ́n máa ń tẹ́ pẹrẹsẹ tí ó sì máa ń sáábà jẹ́ roboto láàrin Iṣi-n-Iṣi mẹfa sí mejidinlogun ní títóbi rẹ̀, pẹlu àwòrán ère tabi ọ̀nà (àpèjúwe)..
wikipedia
yo
Ọpọ́n Ifá tún lè jẹ́ onígun mẹ́rin tí kò dọ́gba, èyí tí kò rí róbótó tán tàbí kí a sọ pé onígun mẹ́rin tí ó dọ́gba..
wikipedia
yo
Òkè àtẹ yìí ni orí ti ìsàlẹ̀ ọpọ́n náà jẹ́, ẹsẹ̀ tí ó súnmọ́ oníyẹ̀míwò jùlọ..
wikipedia
yo
Orí ọpọ́n ni àwòrán eré èṣù máa ń wà, òjíṣẹ́ ifá àti àwọn irúnmọlẹ̀ tókù..
wikipedia
yo
Àwọn àtẹ lè ní àlékún àwòrán eré èṣù, a sì ti rí àtẹ tí ó ní ojú meji, mẹrin, mẹjọ ati mẹrindinlogun rí..
wikipedia
yo
Ni ibi ti o ba ti waye bayii owo ẹyọ ni a fi maa n mọ ori ọpọn, owo ẹyọ yìí naa ni a fi maa n tan iyẹrọsun loju ọpọn naa.Ninu ọpọ́n, babaláwo a da ikin ifa merindinlogun tabi obi merindinlogun si ibi pẹrẹsẹ igi yii, o si maa n sọ mẹjọ ti yoo jade ninu Otalélúgba-o-din-mẹrin ẹ̀yà Odu ti o le fihan..
wikipedia
yo
Àmì yìí ni orí tí wọ́n ṣe déédé ara tí wọ́n gbọdọ̀ kí, tí yóò sì wà ní ìbámu pẹ̀lú ìṣòro ayé ẹni tí ó ṣe àyẹ̀wò..
wikipedia
yo
Nínú ọ̀pọ̀ ìsẹ̀ní ṣeṣe àyẹ̀wò tí a mọ̀ sí ìtọ́jú ti rọ́pò ikin ifa tàbí òbí, tí a fi pamọ́ fún ìbéèrè tí ó ṣe kókóàwọn ìtọ́jú sí..
wikipedia
yo
Àṣà ìsọmọlórúkọ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn àṣà ilẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Gbogbo ohun tí Ọlọrun dá pátá ló ni orúkọ tí wọn ń jẹ́..
wikipedia
yo
kí a bá lè dá ẹnìkọ̀ọ̀kan mọ̀ ni a ṣe máa ń fún wọn lórúkọ..
wikipedia
yo
Yorùbá gbàgbọ́ pé orúkọ a máa fi bi ọmọ ṣe jẹ́ han, orúkọ a si máa ro ọmọ, àti pé orúkọ ọmọ ni ijánu ọmọ..
wikipedia
yo
Orísirísi akiyesi ni àwọn òbí máa ń ṣe kí wọ́n tó lè pinnu orúkọ tí wọ́n máa fún ọmọ..
wikipedia
yo
Wọ́n máa ń ṣe akiyesi ipò tí ọmọ wà nígbà tí a bí i, wọ́n tún máa ń ṣe akiyesi ipò tí ẹbí wà lásìkò tí wọ́n bí ọmọ náà, ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹ̀ ní kété tí wọ́n bí ọmọ náà, tabi ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣẹ̀ nígbà tí ìyá rẹ̀ wà ninu oyún ọmọ náà..
wikipedia
yo
Yàtò sí èyí, wọ́n tún máa ń ṣe àkíyèsí ọjọ àti àsìkò tí ọmọ náà wáyé..
wikipedia
yo
Irúfẹ́ àwọn àkíyèsí yìí ló bí òwe kan tí àwọn Yorùbá máa ń pa tó sọ pé “Ilé là ń wò ká tó sọmọ lórúkọ”.Ìgbàgbọ́ Yorùbá ni pé orúkọ tí a sọ ọmọ a máa kó ipa pàtàkì nínú ìgbésíayé ọmọ..
wikipedia
yo
Yàtọ̀ sí èyí, wọ́n gbàgbọ́ pé bí orúkọ ọmọ bá ṣe rí ni ọmọ náà yóò hùwà, àti pé orúkọ ọmọ ní í rọ ọmọ..
wikipedia
yo
Èyí jẹ yọ nínú òwe Yorùbá kan tó sọ pé “A sọ ọmọ ni sọ́de, ó dé, a sọ ọmọ ní sóbọ̀, ó bọ́, a sọ ọmọ ní Sórìnlọ, ó lọ, kò wálẹ̀ mọ, ta ni kò ṣàìmọ̀ pé orúkọ ọmọ ní í rọ ọmọ”.Ẹ̀tọ́ ìsọmọlórúkọ kí ọjọ́ ìsọmọlórúkọ tó pé, oríṣiríṣi orúkọ ni àwọn Yorùbá máa ń pe ọmọ titun..
wikipedia
yo
Wọ́n a máa pè é ní túnfúlù, ìkòkò, aròbó, Kóǹkólóyo, àlejò..
wikipedia
yo
Ní ilẹ̀ Yorùbá, láyé àtijọ́, ọjọ́ kẹsàn-án ni wọ́n máa ń sọ ọmọkùnrin lórúkọ, ọjọ́ keje ni wọ́n ń sọ ọmọbìnrin lórúkọ, ọjọ́ kẹlú ní Mohn sì n sọ ibeji ní orúkọ..
wikipedia
yo
Ṣùgbọ́n lóde òní, ọjọ́ kẹjọ ni wọ́n ń sọ ọmọ lórúkọ, yálà ọkùnrin, obìnrin tàbí ìbejì.Àwọn ohun èlò ìsọmọlórúkọ obì- ó dúró fún ẹ̀mí gígùn..
wikipedia
yo
Wọn a máa ṣàdúrà pé “Òbí ní í bíkú, òbí ní í bárún, obì yóò bí ọ sáyé, kò ní bí ọ sọ́rùn”.
wikipedia
yo
Wọn a sì máa ṣàdúrà pé “ataare kì í di tí ẹ láàbò, kíkún ní ilé ataare ń kùn, ilé rẹ yóò kún fún ọmọ rẹpẹtẹ, ọ̀ọ̀dẹ̀ rẹ yóò dọ́jà”.
wikipedia
yo
Wọ́n a máa ṣàdúrà pé “ládùn-ládùn là á bá nílé aláadùn, ìbànújẹ́ kò ní wọlé tọ̀ ọ́, láṣẹ Elédùà”.
wikipedia
yo
Orógbó- O dúró fún ẹ̀mí gígùn, wọn a sì máa ṣàdúrà pé “orógbó ní í gbó ní sáyé, wà á gbó, wà á tó, wá a pẹ́ láyé”.
wikipedia
yo
Ọtí- ó dúró fún àjíǹde ara, wọn a sì máa gbàdúrà pé “Ọmọ náà kò ní tẹ́ láwùjọ, ẹnu otí kì í tí, o ò ní ti láyé, ibi ayọ̀ là ń bọ̀tí, a ò ní bá ọ níbi ìbànújẹ́ o”.
wikipedia
yo
Wọ́n a sì máa gbàdúrà pé “Iyọ̀ ní í mọ́bẹ́ẹ̀, ayé rẹ̀ a fọ́fọ́, ayé rẹ̀ ò ní date o, ayé rẹ̀ ò ní dòbu o”.
wikipedia
yo
Wọ́n a sì máa gbàdúrà pé “Dídùn dídùn là á balẹ̀ yín, ẹnìkan kì í fọyín sẹ́nu kò tutọ́ ẹ sọnù, a kì í fọyín sẹ́nu ká pòṣé, ayé rẹ yóò dùn joyin lọ”.
wikipedia
yo
Wọ́n a sì máa gbàdúrà pé “Orí lẹja fi ń làbù jà, orí kì í fọ́ ẹja lálẹ́ odò, orí rẹ̀ kó má ṣe gbàbọ̀dè fún ọ, orí rẹ̀ kò máà sẹ́lẹgbẹ́ lẹ́yìn rẹ̀ o”.
wikipedia
yo
Wọn a sì máa gbàdúrà pé “Ìkorò kò ni wọ ayé rẹ, ayé rẹ yóò dùn títí”.
wikipedia
yo
Wọ́n a sì máa gbàdúrà pé “ẹnìkan kì í bómi ṣọ̀tá, omi la bù wẹ̀, omi la bù mu, kó Mọ́mì ayé gbọ́, kó Mọ́mì ayé tó, kò ní sá pa ọ́ lórí o, kò sì ní gbòdì lára rẹ̀ láṣẹ Elédùà”.
wikipedia
yo
Wọ́n á sì máa gbàdúrà pé “epo nírọ́jú ọbẹ̀, bí ó bá ń jẹ ẹ́ lọ́bẹ̀, yóò máa bá ọ lára mu, ààrò kì í gbóná dalẹ́, ìgbóná ò ní wọlé tọ̀ ọ́ wá”.
wikipedia
yo
Wọn a si maa gbadura pe "Aje yoo fi ile rẹ se ibugbe, níná ni tọwọ́, o ò rọ́wọ́ fi ṣe ayé rẹ, o ò ní tàwọna, o ò ní wojú olójú ko to rowọ́ ná, ojú owó ko ni pọn ọ”.Òjò orúkọ ni ilẹ Yorubaoruko àmútorún eyi ni orukọ ti a fun ọmọ nitori ọna ti ọmọ naa gba waye, tabi asiko ti o wa sáyé..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ àti ìtumọ̀ wọn ni; Taiwo- ọmọ tí a kọ́kọ́ bí ninu ibeji (oun ni o kókó to aye wó ki ekeji re to tele) Kehinde- ọmọ ti won bi tele Taiwo ni ori ìkúnlẹ̀ kan.
wikipedia
yo
Tí wọ́hn tún maa ń pè ní ìyìpọ̀ olú Ojo- ọmọ tó gbé ibi rẹ̀ runrun wáyé.
wikipedia
yo
Amúṣan- ọmọkùnrin tí a bí pẹ̀lú iṣan eegun lọ́wọ́ rẹ̀.
wikipedia
yo
Ìlọ̀rí- Ọmọ tí ìyá rẹ̀ kò ṣe nǹkan oṣù tó fi lóyún rẹ̀.
wikipedia
yo
Òdú- ọmọ tó ní ìka ọwọ́ mẹ́fà òkè- ọmọ tó ń dákú tí wọ́n bá dá dùbúlẹ̀ rò ó lóúnjẹ.
wikipedia
yo
Òní- ọmọ tó máa ń ké tọ̀sán tòru.Orúkọ àbísọ èyí ni orúkọ tí wọ́n sọ ọmọ ní ìbámu pẹ̀lú ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣe nígbà tí ìyá ọmọ náà wà nínú oyún tàbí nígbà tí a bí i..
wikipedia
yo
Àpẹẹrẹ àwọn orúkọ wọ̀nyí àti ìtumọ̀ rẹ̀ ni; Babátúndé/ Babajide/ Babawale ọmọkùnrin tí a bí lẹ́yìn tí baba-bàbá rẹ̀ kú.
wikipedia
yo
Yetunde/ Yejídé/ Yéwándé/ Iyabo- ọmọbìnrin tí a bí lẹ́yìn tí ìyá-bàbá rẹ kú.
wikipedia
yo
Babarímisá/ Babáyẹjú- Ọmọkùnrin tí wọ́n bí ni geere tí baba rẹ̀ kú.
wikipedia
yo
Iyerímisá-Misa ọmọbinrin tí wọ́n bí ní geere tí baba rẹ̀ kú.
wikipedia
yo
Àbí-ọ̀nà ọmọ tí a bí sójú ọ̀nà(ó lè jẹ́ lórí ìrìn-àjò) ayọ̀lọ́rọ̀/ àyọ̀mikún/ ayokún- ọmọ tí a bí nígbà tí gbogbo nǹkan ń lọ fún àwọn ẹbí rẹ̀.
wikipedia
yo