cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Ẹkùndayọ̀ ọmọ tí wọ́n bí lẹ́yìn tí OLUWA fòpin sí ìbànújẹ́ àwọn òbí rẹ̀. | wikipedia | yo |
Ọmọlàjà- ọmọ tí a bí lásìkò tí baba àti ìyá rẹ̀ ń jà, tó jẹ́ pé ìbí rẹ̀ ló la ìjà náà. | wikipedia | yo |
AbíDemi- ọmọ tí bàbá rẹ̀ kò sí nílẹ̀ nígbà tí ìyá rẹ̀ bí i. | wikipedia | yo |
FiOmidan- ọmọ tí a bí nígbà tí ìjà wà láàárín àwọn òbí rẹ̀ tàbí ẹbí. | wikipedia | yo |
Kúpọ̀nìyí- ọmọ tí a bí lẹ́yìn tí aláfẹ̀yìntì ninu ẹbí kú. | wikipedia | yo |
Ìbídùn- ọmọ ti ìkúnlẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìrọ̀rùn fún ìyá rẹ̀.Orúkọ àbísọ ní ìbámu pẹ̀lú ẹṣin ìdílé oníṣàngó- Ṣàngóṣèyí, Ṣàngógbemi, Ṣàngóilẹ̀, Ṣàngówunmi, Ṣàngófúnlé, Ṣàngónìyí, Ṣàngópọ́nlé. | wikipedia | yo |
Ìdílé ológun-un- Ogundélé, Ogunjìnmí, Ogunyemi, Ògúnwale, Ògúnwunmi, Ogundare, Ogundies. | wikipedia | yo |
Ìdílé ọlọ́rọ̀- Ọrọ̀wọlé, Orogbemi, OroFunke, Orobiyìí, Oroyẹmí, Abioro, Auniwa. | wikipedia | yo |
Ìdílé elẹ̀ṣù- Èṣùgbemi, Èṣùṣèyí, ÈṣùFunke, EṣúKemi, Èṣùwale, Èṣùbiyìí, Èṣùbunmi, Eṣúkunle. | wikipedia | yo |
Ìdílé olósùn- osùnFúnkẹ́, osùnṣèyí, osùnwunmi, èdèkòyédè, OsunTádé, Òṣúnlékè. | wikipedia | yo |
Idilé ọlọ́bàtálá- àlàyémi, abọ̀rìṣàde, Efuntunde, Bamgbàlà, EfunYemi. | wikipedia | yo |
Ìdílé Olórìṣà-oko- Sotacles, Sokoya, Sobowale, Ẹfúnṣetán, Efunkọ́, Tejuoso. | wikipedia | yo |
Idilé Aláwọ̀- Awogbemi, Awolola, Apéjú, Iroko, Iwile, ìfàlọ́wọ́, FáSina | wikipedia | yo |
ìdílé eléégún- ọ̀jẹ́làdé, Osubi, Aabẹde, Edunjobí, Oroko, Oroko, Opàfunmi, Oetotọ́. àbísọ ni ibamu pèlú idile.. | wikipedia | yo |
gbaara tí a bá ti sọ ọmọ náà lórúkọ ni a o fun un loriki.. | wikipedia | yo |
Orúkọ yìí ni wọ́n á fi máa kí ọmọ náà kí orí rẹ̀ bá le máa wú.Orúkọ oríkì fún ọkùnrin Alamu Aremu Ìṣọ̀lá Àkànní alágbára Àjàní Akanmú Akanbí Adisa Àlàó Alade Ajao Àkànjíorúkọ oríkì fún obìnrin Aroko Àríkẹ́ àpèkẹ́ Abeke Àdùkẹ́ Alátinú àyọkà ajíke Abeni Àṣàbí àjọkẹ́ Àkànkẹ́ ìnagijẹ èyí ó sí lára àwọn orúkọ tí Yorùbá máa ń sọ ọmọ níjọ kẹjọ.. | wikipedia | yo |
Àwọn ọ̀rẹ́ tàbí ẹbí ló máa ń fún ènìyàn ní irúfẹ́ orúkọ yìí.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ orúkọ tó máa ń wáyé nípa ìrísí, ìṣesí àti ìrìnsí ẹni tí a fẹ́ fún ní orúkọ yìí.. | wikipedia | yo |
Anataos George Leventis (; December 1902 – October 25, 1978) je omo ile Girikiti o je awon alakale ti o da oniruuru ise kale Jaakiri agbaye, paa paa julo ile Adulawo ti o fi kan orile ede .Naijiria, Naijiria, ti iyen (Nigeria) Plc, ti oba Aláké ti ile Egba oba LaDapo Ademola si fi je oye agbaje ile ile Egba. omo re kan soso ti o je bere fun ti oruko re n je ejo fo ni o fe oloselu kan ti oruko re n je osere paparysville kan lati lati o je aare-ede Cyprus tele tele ri aye re bi ilu ni awon abúlé ni awon agbaboolu ni ileto District, ni ilu TroDO Mountains.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ̀ jẹ́ Mínísítà fún ilé ìjọsìnn Greek Orthodox Church tí ó sì tún jẹ́ olùkọ́ nílé ìjọsìn kan náà.Leventis lọ sí ilé -ẹ̀kọ́ Mitsis Commercial ní tí ó pé ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16), ó ṣàtìpó lọ sí ilẹ̀ ṣe láti lọ wá iṣẹ́ àti láti láti láti ìlúkẹ́kọ̀ọ́.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1920, ó rí ànfàní láti ṣiṣẹ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí ọlọ́jà ní ńwáni, Lólọ́pọ̀ Cross River.Ìgbòkè-gbodò iṣẹ́ rẹ̀ ní ọdún 1922, Leventis dara pọ̀ mọ́ iké iṣẹ́ a.J.. | wikipedia | yo |
Ó ní ìbáṣepọ̀ tó lọ́ọ̀rìn pẹ̀lú àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà nígbà tí ó ń ṣiṣẹ́ ní Abẹ́òkúta.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó ìbáṣepọ̀ rẹ̀ fesẹ̀jú múlẹ̀ tán pẹ̀lú Ọ̀gbẹni G.B.. | wikipedia | yo |
Olliamòfin, Leventis ṣiṣẹ́ pẹ̀lú iké iṣẹ́ aládàpọ̀ títí ó fi di adarí àgbà fún ilé iṣẹ́ G.. | wikipedia | yo |
Ollivant tí ó wà ní orílẹ̀ èdè Ghana. Ní ọdún1937, ó kúrò nílé iṣẹ́ náà lẹ́yìn tí United Africa Company ra ilé iṣẹ́ náà.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí,,Leventis lọ dá ilé iṣẹ́ tirẹ̀ kalẹ̀, tí ó sì ń ra ọjà tí ilé iṣẹ́ kan bá ti ṣe jáde fún títà, tí ó sì ń rí ìrànlọ́wọ́ owó láti ọwọ́ ọ̀dọ̀ àwọnBritish cotton lọ́dọọdún" | wikipedia | yo |
Bákan náà ni ó tún rí Iraanwò owó lọ́wọ́ ọmọ ìyá rẹ̀ kan tí ó ń jẹ C.p.. | wikipedia | yo |
Leventis, eni ti o da ẹka ti ilẹ̀ Nàìjíríà kalẹ̀ ní ọdún1942, pẹ̀lú ọrẹ rẹ̀ g.Ẹ.. | wikipedia | yo |
Keralakis. Bí orílẹ̀ èdè Ghana, Leventis káànú àwọn ajìjà-n-gbara tí wọ́n jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Ghana.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí rògbòdìyàn bá ṣẹlẹ̀, láàrin ìlú, ọ̀pọ ilé-ìtajà àwọn àtòun-rìnwá ni wọ́n ma ń tì pa tàbí kí wọ́n sun wọ́n níná àyàfi ti ọ̀gbẹ́ni Lẹ́vẹ́ntíìsìì ni wọ́n ma ń yọ̀ǹda fún láti tajà ní gbogbo àsìkò náà. Wọ́n fi ṣe aṣojú orílẹ̀-èdè Ghana sí orílẹ̀-èdè fabe nígbà tí Nmahmah di Ààrẹ orílẹ̀-èdè Ghana.Ní ọdún1940, ilé iṣẹ́ rẹ̀ dojú kọ àwọn ìsọ̀rọ̀ó kan, ìjọba ilẹ̀ UK fòté lé iye ẹ̀gbọ̀n òwú ó le wọlé láti ilẹ̀ adúláwọ̀ léte léte àti dá sí okòwò aṣọ àti epo-rọ̀bì àríwá ilẹ̀ adúláwọ̀, lẹ́yìn ìparí ogun àgbáyé ẹlẹ́kejì “World War II” , wọn kò rí Ọjà rà tàbí tà mọ́, ìpèníjà wọ̀nyí mú ìfàsẹ́yìn V iṣẹ́ A.G Leventis láyí nã tan rẹ̀ tán nílẹ̀ Nàìjíríà, tí ó lé ni a.G.. | wikipedia | yo |
Láàrín ọdún díẹ̀, okòwò ilẹ̀ Nàìjíríà yí bírí kúrò lórí okòwò ẹ̀gbọ̀n owú sí òwò kátà-kárà pẹ̀lú oríṣiríṣi ọjà.. | wikipedia | yo |
Níparí ọdún 1940, ilé-iṣẹ́ náà pàwọ̀dà látàrí àyípadà òwò lásìkò yí.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1960, ìjọba ilẹ̀n Nàìjíríà gbéṣé ìkọ́lé ìtura kanó fún ilé-iṣẹ́ àkójọpọ̀ Leventis pé kíó kọ́ó kọ́ ilé ìtura ti ìjọba ti ìjọba orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ìyẹn "Federal Palace Hotel" gẹ́gẹ́ bí ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà ṣe bèrè fun. ilé ìtura náà dúró fún ilé ìgbé àwọn ará iké sí ayẹyẹ ayẹyẹ òmìnira eNàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó di ọdún 1960, ilé-iṣẹ́ rẹ̀ ti gbèrú sókè tíbá sì di ọ̀kan gboogi lára àwọn ilé isẹ́ ìtajà ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ó gbìyànjú láti yí ilé iṣẹ́ rẹ̀ padà kúrò ní ilé ìtajà lásán padà sí ilé iṣẹ́ àkànṣe àti ìkọ́pamọ́ àwọn ọjà pàtàkì. Ní àsìkò yí, ilé iṣẹ́ rẹ̀ gbèrú sí látàrí àyípadà tí ó débá okòwò ilẹ̀ Nàìjíríà, àti bí àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n jẹ́ ajìjà-n-gbara fún òmìnira ilẹ̀ Nàìjíríà ṣe jókòó lé iṣẹ́ òwò ṣíṣe nílé baba wọn ní àsìkò ọdún 1970.. | wikipedia | yo |
Èyí ló fún Lẹ́vẹ́ntíìsì lánfàní láti jẹ́ kí àwọn iní báárà rẹ̀ àtibáwọn ènìyàn míràn Obtún fẹ́ràn rẹ̀ síi látàrí bí ó ṣe ń fa ojú wọn mọ́ra nípa títajà lówó pọ́ọ́kú fún wọn.. | wikipedia | yo |
Yàtọ̀ sí èyí, ó tú tún ṣe ìkúnlápá fún ègbẹ́báwọn ajìjà-n-gbara nílẹ̀bNàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Látàrí ìbáṣepọ̀ tó dán mọ́rán tí ó wà láàrín òun àti Olùṣọ́ Àgùtàn Makarios III, wọ́n fi ṣe aṣojú Ilẹ̀ Cyorus ai àjọ UNESCO, tí ó sì tún gba àmì ẹ̀yẹ St.. | wikipedia | yo |
Barnabas.Iṣẹ́ ìtọrẹ-àánú rẹ̀ wọn dá àjọ (Leventis Foundation) ní ọdún 1979kalẹ̀ ẹ̀yin tí a.G Levetis kú ní ọdún 1978.. | wikipedia | yo |
Àjọ náà ṣe iṣẹ́ íore àánú púpọ̀ lórúkọ rẹ̀ nípa ríra àwọn àwòrán olówó iyebíye tó ṣàfihàn àṣà àti ìṣẹ̀ṣe sínú ilé ìṣura ohun àbáláyé ilẹ̀ Cyprus, Greec àti ọ̀pọ̀ ilé ìṣura lágbàáyé lápapọ̀fún àǹfàní àwọn Kniwàádìí ìmọ̀.. | wikipedia | yo |
Àjọ yí tún ń ṣagbátẹrù fún àwọn ohun tí ó jẹ mọ́ àṣà , bẹ́ẹ̀ náà ni ó tún ń pèsè ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè kúrò ní Fásitì àmọ́ tí wọ́n ṣì ń ṣe iṣẹ́ ìwádí ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ìmọ̀ Abájìjì àti ìmọ̀ iṣẹ́ àgbẹ̀.. Bákan náà ni àjọ yí tú ṣe ìkúnlápá fú ìmọ̀ ìwádìí nípa ààbò àwùjọ àti ìwádí nípa iṣẹ́ ìlera.Ní ọdún 1987 wọ́n fi àwòrán à.G.. | wikipedia | yo |
Leventisje ojogbon agba ni ile eko Cambridge University niGreek nigba ti won o ti ojogbon asa asa asa a.. | wikipedia | yo |
Leventis professor of Greek Culture.Ìgbésí ayé rẹ̀ a le tọpasẹ̀ ìran rẹ padà sí ọ̀rúndún kejìdínlógún (28th century).. | wikipedia | yo |
Nígbà tí bàbá ńbí rẹ̀ ṣàtìpó lọ sí Peloponnese gẹ́gẹ́ bí ìtàn 'v' ṣe gbé ní 1770.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí wọ́n fẹ́ bí, ọ̀pọ̀ àwọn Bíṣọ́ọ̀bù tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ ilé ìjọsìn Othodox ti Jerusálẹ́mù àti Antioch, àti àwọn alàgbà ilé ìjọsìn as Cyprus.Wọ́n bí ní oṣù Kejìlá ọdún 1902 ní ìlú Lemymy, ní orílẹ̀ èdè Cyprus.. | wikipedia | yo |
Leventis ìyẹn (Foundation Gallery) níbi tí ọ̀pọ̀ ìhun ìṣura àbáláyé bí ère Cypriot, Terracotta, vases, jewelry àti coins tí a lè tọpasẹ̀ rẹ̀ padà sí ọ̀rùndún kẹrin àti ọ̀rùndún karùún ṣájú kí wọ́n tó bí Jésù.. | wikipedia | yo |
Àjọ náà tún ṣèrànwọ́ nípa sísan owó fún àwọn ihun ìṣura ti ó jẹ mọ́ ilẹ̀ Giriki, Louvre ní ilẹ̀ Paris Parisàti ilẹ̀ ìṣura ìṣura FitzWilliam ti ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ àgbàko Cambridge University, àti àwọn mìíràn gẹ́gẹ́ bí ìjábọ̀ ọdọdún wọn ti wí.. | wikipedia | yo |
Ní ilẹ̀ Greece, àjọ náà tí náwó lọ́pọ̀lọpọ̀ sórí ìṣe Aáraọ́lọ́jì tó pọ̀brẹpẹtẹ.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Hanb Ngozi Onyejí jẹ́ sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ orí Asọ̀rọ̀-mágbèsì ni ilẹ̀ Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Temitope Adeyemi jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ede Nàìjíríà tí ó jẹ́ sọ̀rọ̀ soro orí ẹ̀rọ Alátaìkàn sí.. | wikipedia | yo |
‘Ọmọ ọ̀nà-adigun" jẹ́ sọ̀rọ̀ sọ́rọ̀ orí ẹ̀rọ asọ̀rọ̀-mágbèsì, àti ẹ̀rọ ayélujára ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Olùka sí.. | wikipedia | yo |
ìṣímeme ejò-q-Só jẹ́ olùkọ́ tí ó ma ń kọ́ àwọn ọmọdé tàbí ọ̀dọ́ pàápàá jùlọ àwọn ọmọ obìnrin tàbí wúndíá lórí bí wọ́n ṣe lè gbé ìgbé ayé ìrọ̀rùn gegege bí ohun èlò oas àwùjọ.ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Lily Anińyéi jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti olùdásílẹ̀ 'Greenroom Nigeria'.Olùka sí.. | wikipedia | yo |
Cma Cgmnì ilé-iṣé ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ kan láti Faransé, ó jẹ́ ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ gíga ti káríayé ti transPorter.. | wikipedia | yo |
Sparj alágbàtà ti ilu okeere ti n ta awọn ọja abuda gegebi ounje, awọn onigbọwọ, ati awọn tikẹti lọ́tìrì.. | wikipedia | yo |
Ọ̀pẹ̀lẹ̀ (pípè rẹ̀ Otèlé tàbí Ocuele ní Látìnì-Amẹrika) ni okùn ìṣàyẹ̀wò tí wọ́n ń lò nínú ẹ̀sìn ìbílẹ̀ Adúláwọ̀ àti àwọn akátá-Amẹrika, pàápàá jùlọ nínú Ifá àti ìṣẹ̀ṣe Yorùbá.Babaláwo (oniyẹ̀míwò) máa ń lo ọ̀pẹ̀lẹ̀ láti le sọ̀rọ̀ pọ̀ pẹ̀lú Òòṣà Ọgbọ́n/ìmọ̀ (Ọ̀rúnmìlà) nínú ìṣẹ̀ṣe Yorùbá Ẹni tí ó le ṣe àfihàn okùnfà àti ojútùú sí ìsọ̀rí àdáni àti gbogbogbò yóò sì fi mú ìrọ̀rùn padà wá sí ayé onítọ̀hùn nípa titun ìpín àti/tàbí orí (òòṣà ẹnìkọ̀ọ̀kan) ẹni ṣẹ.. | wikipedia | yo |
Ọ̀pẹ̀lẹ̀ jẹ́ ohun èlò àyẹ̀wò kékeré tí àwọn babaláwo ń lò; wọ́n gbàgbọ́ pé “Olùrànlọ́wọ́” tàbí “Ẹrú” Ọ̀rúnmìlà ni, ẹni tí ń ṣe alagbasọ ìfẹ́ Ọ̀rúnmìlà fún babaláwo tí ó sì tún ń mú láti ọ̀dọ̀ babaláwo padà fún Orunmila.. | wikipedia | yo |
Fún àyẹ̀wò tí ó bá jẹmọ́ àyẹ̀wò ohun pàtàkì míràn tàbí ohun pàtàkì ọjọ́ iwájú nípa olùṣàyẹ̀wò tàbí fún ìpinnu pàtàkì, babaláwo yóò lọ ikin Ifá, èyí tí wọ́n gbà pé ó jẹ́ olùpòpò Ọ̀rúnmìlà... | wikipedia | yo |
Aṣọ Òfì tàbi Aṣọ Òkè jẹ́ aṣọ olówùú tí a fọwọ́ hun láti ọwọ́ ẹ̀yà Yorùbá ti Ìwọ̀ Oòrùn Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ọkùnrin ni ó ṣáábà máa ń hun-ún, wọ́n a máa fi ṣe ẹ̀wù tí a ń pè ní agbádá, ìró obìrin tí a ń pè ní ìró, àti àkéte ọkùnrin tí a ń pè ní Afìlà inú àṣà ìpínlẹ̀ Òǹdó,ìpínlẹ̀ Ògùn, Ìpínlẹ̀ Èkìtì, Ìpínlẹ̀ Èkó àti Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ìwọ̀ Oòrùn Nàìjíríà.Ọ̀nà tí an gbà hun aṣọ òkè kò fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, àmọ́ ọgbọ́n àti ọ̀nà Igbójajáde ti rí sí yíyí wíwúwo àti nínípọn aṣọ òkè àti kí ó ṣe é wọn fún ìgbafẹ́ aṣọ òkè àwọn ọ̀nà mìíràn tí àwọn ahunṣọ ń lò láti fi lè jẹ́ kí aṣọ ìbílẹ̀ ayé àtijọ́ yìí di ti ìgbàlódé ni ṣíṣe “Hkoro àti àlọ́pọ̀ àwòrán ọ̀nà ẹranko àti òdòdó fún yíyọ àwọn igun àti Jilọ́láerika kan, tí ó dára fún iṣẹ́ ọ̀nà nípa èrò ayára-bí-àṣá.. | wikipedia | yo |
Ìpilẹ̀ ọ̀nà ìbílẹ̀ yóò ṣe bí ẹní wa láti ara ààlọ̀ àti ìtàn àròsọ.. | wikipedia | yo |
Gbogbo àwọn ẹlẹ́ṣin Yorùbá náà máa ń wọ aṣọ òkè àti fìlà.. | wikipedia | yo |
UFM je Iṣowo Iṣowo ti Awọn orilẹ-ede Mediterranean ni ibi ti Aladani Arab ati European Union je eya egbe ti agbede agbede, UFM je ile-isowo isowo ti o ni Iṣowo ni Awọn orilẹ-ede United Nations.. | wikipedia | yo |
Orúkọ Yorùbá jẹ́ ohun pàtàkì tí àwọn Yorùbá ń lọ jákè-jádò gbogbo ibi tí wọ́n ti ń sọ èdè Yorùbá bí Ìbìní, àti Nàìjíríà.Nípasẹ̀ iṣẹ́ àwọn baba ńlá bàbá àwọn Yorùbá, Ee— N fún ọmọ wọn lórúkọ níbi ayẹyẹ tí ó máa ń wáyé ní Ọjọ́ Kẹẹ̀jọ Lẹ́yìn ìbímọ.Àwọn orúkọ àwọn ọmọ jẹ́ àṣà àtọwọ́dọ́wọ́ nípa ifá dídá tí ọ̀pọ̀ babaláwo bá dá, ṣùgbọ́n ní ayé òde-òní, orúkọ ọmọ tún lè wá láti ọ̀dọ̀ àwọn tí ó bá ní ipò tọ̀gá nínú ẹbí pẹ̀lú bàbá,Ìyá àwọn òbí méjèèjì tàbí ẹni tí ó súnmọ́ wọn gbágbá.Ìyá àti Bàbá,àti Aláṣún-ún-mọ̀ wọ́n lè fún ọmọ tàbí àwọn ọmọ ni orúkọ tọba wù wọ́n. Orúkọ ọmọ ṣáá máa ń wá láti ọ̀dọ̀ àwọn òbí méjèèjì ìyá àti bàbá ọmọ àti àwọn òbí tó bí òbí méjèèjì yí wọn bí ọmọ tí wọ́n fẹ́ sọ lórúkọ.Orúkọ ìbílẹ̀ tí a dífá fún láti ọ̀dọ̀ babaláwo ń ṣe àfihàn òrìṣà tó ń ṣe atọ́nà ọmọ náà wá sáyé, yálà ọmọ náà jẹ́ àtúnbí óò nílẹ̀ àtipé kádàrá ọmọ àti nípa ti ẹ̀mí tí ó lẹ́tọ̀ọ́ sí,tí ó máa ran ọmọ náà lọ́wọ́ láti lè jẹ́ kí ó tẹ̀ ẹ́ lọ́wọ́.Ayẹyẹ àkọ́kọ́ kan tún wá fún ìyá àti ìyá àti bàbá nìkan níbi tí orúkọ àti èèwọ̀ yóò ti máa jẹ́ fífún ọmọ àti òbí rẹ̀,àti àbá lórí ohun tí ọmọ náà máa nílò láti fi ṣe àṣeyọrí.Ọjọ́ díẹ̀ lẹ́yìn ìnáwó àwùjọ tí àṣẹ àti àríyá ti wáyé tí* | wikipedia | yo |
Àpẹẹrẹ ni ẹ̀yinfúnjọ̀wọ́,ẹ̀yin ajíran,ajíSafe,ọ̀pẹ́lẹ́ńgẹ́ tutu,àgbòtíkú, ìbàdí ìbàdí àrán àti Bigi.. | wikipedia | yo |
EJI ninu orukọ yàráọ̀ wa Yorùbá to gbajumọ ju ni Taiwo(tabi Taye) ati Kehinde ti won fun awọn ibeji ni pataki.. | wikipedia | yo |
Orúkọ ipasẹ̀ tún lè ṣàkàwé ipò tí ìdílé náà wà láwùjọ(àpẹẹrẹ “Adewale” orúkọ ìdílé ọba àtàtà)Ó tún lè ṣàkàwé iṣẹ́ abínibí Ìdílé kan(àpẹẹrẹ”Akọ́",àwọn alágbẹ̀dẹ).Yorùbá tún ni oríkì irú èyí tí àwọn àkòríkì máa ń lò láti tẹpẹlẹ mọ́ àṣeyọrí Aṣáájú ti oríṣìíríṣìí ìdílé.Oríkì tún lè jẹ́ ẹlẹ́yọ ọ̀rọ̀ bí i "Àdùnní” kí ó jẹ́ ẹsẹ ìwé tàbí játùnú.Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé kì í ṣe ipa àtàtà ni ó ń kó nínú orúkọ gidi,oríkì máa ń ṣáábà jẹ́ lílò ní ẹgbẹ́ kan ,Ó máa ń sáábà jẹ́ ohun tí gbogbogbò mọ̀ mọ́ọ̀yàn ní àkókò kan.Púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn ní àwọn ará ìlú mìíràn lé dámọ̀ kódà ìdílé wọn nípa lílo oríkì òkun ìrandíran wọn.Iṣẹ́ kékeré ni yíyan orúkọ níṣẹ́yí nítorí kòsí àkójọpọ̀ orúkọ Yorùbá tó pè.Síbẹ̀síbẹ̀ iṣẹ́ àgbéṣe titun akẹ́kọ̀ọ́ akẹ́kọ̀ọ́ èdè ti bẹ̀rẹ̀ láti ṣe gbogbo orúkọ Yorùbá sí kíkọ sílẹ̀ sínú ìwé Arídìí árídìí ní ti ìlànà ọnà ìgbà ròyìn.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
dòdò Ikire jẹ oúnjẹ ìbílẹ̀ láti ìlú Ikire ní gúúsù-ìlà oòrùn ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
dòdò Ìkirè dúdú, ó sì tún yí roboto tàbí onígun òkòtó.Ọ̀gẹ̀dẹ̀ dòdò, èyí tí wọ́n ti bó èèpo rẹ̀, tí wọ́n gé tì wọ́n sì dín dáadáa ni wọ́n ń pè ní dòdò ní àwọn apá ibìkan ní Nàìjíríà.Akọni fi hàn pé dòdò íré wáyé láti ara àyẹ̀wò láti ọ̀dọ̀ aláìní, ìyá arúgbó láti ìlú tí wọ́n npè ní Ikire.. | wikipedia | yo |
Ikire jẹ́ ìlú kan ni gúúsù ila-oorun agbègbè Nàìjíríà láàrín ìlú Ìbàdàn sí ilú Ilé-Ifẹ̀, ni ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.Ìyá arúgbó yìí kòní oúnjẹ àyàfi ọ̀gẹ̀dẹ̀ àgbàgbà àpọnra, èyí tí ọba tìka lára rẹ̀ dànù, àmọ́ ó pinu láti ṣe ọ̀pọ̀ míràn kí ó sì pín fún àwọn aláàdúgbò rẹ̀.Apẹ̀yìndà rẹ̀ ni ohun tí amọ̀ sì dòdò íjí, orúkọ tí ó wáyé láti ìlú tí ó ti ṣẹ̀ wá.. | wikipedia | yo |
Wọ́n maa ń ṣáábà tà a ní gúúsù-ẹ̀ òòò apá Nàíjíríà.àwọn ìtọ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
Àbíkú Àbíkú jẹ́ orúkọ Yorùbá ti ó lè túmọ̀ si ‘ẹni ti wọn ń bi ti ó n kú lọ́pọ̀ ìgbà’.Àbíkú ń tọ́ka si èmi ẹni tókù yálà ọmọdé tàbi ẹni ti ó kú ki ó tó dàgbà.. | wikipedia | yo |
Ọmọ tí ó kú kí ó tó di pé ó pé ọmọ ọdún méjìlá ni a lè pè ní àbíkú ọmọdé, bẹ́ẹ̀ kẹ̀,ẹni tí ó kú nigbà tí ó dàgbà tí àwọn òbí rẹ̀ kò ní agbára láti bí òmíràn mọ̀ọ́ ni wọ́n ń pè ní àbíkú àgbà.Kò ki ń ṣe wí pé àbíkú nìkan ni ẹ̀mí ọmọ tí ó kú ní kékeré,gẹ́gẹ́ bí ìgbàgbọ́ Yorùbá ni pé èmi náà á padà sí ara ìyá rẹ̀ kan náà ní àìmoye ìgbà lati tún n bi ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà .Ìgbàgbọ́ yìí ni pé èmi náà ni ó pinnu láti dúró “ṣe ayé” síbẹ̀ ó jẹ́ sí ipò (ti iyá )àti ìpọ́njú ìyá rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Èmi fúnra wọn gbàgbọ́ láti gbé nínú igi ẹ̀yà òwú féfé.Lítíréṣọ̀iwe a-ká-kọ́gbọ́n ti ben okri ti ó pè ni"The Famished Road"Ọ̀nà tókù fún ẹbí" da le lórí àbíkú.Ìwé a-kà-kọ́gbọ́n Débọ̀ kótun àbíkú"arọ̀fọ̀ Òṣèlú Nàìjíríà Olówó ológun"dá le lórí àbíkú.Ìwé a-ka-kọ́gbọ́n ọ̀pọ̀ṣàpèjúwe Gerald brom ṣe àpèjúwe ohun èlò ìṣeré tó ń jà tako àbíkú,gẹ́gẹ́ Pulse ṣe ṣàpèjúwe rẹ̀.co, ọmọ náà wáyé nínú ìwé kíkọ òǹkọ̀wé ara siliNINokùn Gabriela babni,nínú ìwé rẹ̀" kò is Bombaza.. | wikipedia | yo |
Ọ̀rọ̀-àyálò jẹ́ ọ̀rọ̀ kan pàtàkì tí a ya wọnú èdè Yorùbá láti inú èdè mìíràn, ó lè jẹ́ láti inú Gẹ̀ẹ́sì, Lárúbáwá, Hausa àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ kí ó lè bá ohun tí wọ́n fẹ́ mu nínú èdè wọn.Àkíyèsí sì wà pé kò sí èdè tàbí àwùjọ kan tí kì í ya ọ̀rọ̀ láti inú èdè kan, bí Gẹ̀ẹ́sì ṣe yá ọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀ náà ní àwùjọ Yorùbá náà ya ọ̀rọ̀, bí ó sì ṣe wà káàkiri nínú gbogbo èdè àgbáyé.. | wikipedia | yo |
Orísirísi ọ̀nà méjì làá gbà yá ọ̀rọ̀ lò nínú èdè Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Àlọ́ ni ẹ̀yà lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá tí wọ́n fi ń kọ́ àwọn ọmọdé lẹ́kọ̀ọ́ tàbí dá wọn lára yá.. | wikipedia | yo |
O jẹ asa ikomoleko ati idaraya fun awon omode.. | wikipedia | yo |
Àlọ́ lè wáyé nípa sísọ ìtàn kúkúrú akọ́nilọ́gbọ́n tàbí kí ó jẹ́ ìbéèrè àdìtú.Àkókò ìpalọ́alẹ̀, pàápàá jùlọ nígbà tí òṣùpá bá tán ni àwọn àgbà àdúgbò máa ń kó àwọn ọmọdé jọ láti pálọ̀ fún wọn.Ìwúlò àlọ́àlọ jẹ́ ọ̀nà kan pátátí ti àwọn Yorùbá ń gbà láti fojú àwọn ọmọ wọn mọ́lẹ̀ sí ìwà, àṣà, ẹ̀sìn àti láti ṣàgbẹ̀ga fún ìtẹ̀síwájú èdè wọn láti orí ìran kan sí òmíràn.Oríṣi àlọ́àlọ pín sí oríṣi méjì, àkọ́kọ́ ni, àlọ́ àpamọ̀ èkejì ni àlọ́ àpagbé.Àlọ́ àpamọ̀jẹ́ àlọ́ tí Ìapálò yóò pa gẹ́gẹ́ bí ìbéèrè fún àwọn àgbàlòó láti yẹ ọpọlọ wọn wò bóyá wọ́n gbédè, mọ àṣà, mọ ìṣirò, lọ́gbọ̀n àti lè ronú jinlẹ̀ sí èsì àlọ́ náà dára dára. túmọ̀ jẹ́ àlọ́ tí ó ma ń wáyé lẹ́yìn àlọ́ àpamọ̀ tí ó sì kún fún ìtàn, orílẹ̀, orílẹ̀, ìlú tó ti ṣe, teniyan tàbí tẹranko, tí ó sì ma ń ní orin àti ìlú nínú fún ẹ̀kọ́ àti ìdárayá fún gbogbo olùkópa.Ìgbésẹ̀ àlọ́ ti àwọn ọmọdé bá ti àwọn tí kò jọ tí wọ́n sì pagbo, ẹnìkan yóò dúró gẹ́gẹ́ bí apálọ, ẹni yìí lè jẹ́ àgbàlagbà ọkùnrin tàbí obìnrin, bẹ́ẹ̀ ó sì lè jẹ́ ọmọdé lọ́kùnrin tàbí lóbìnrin, tí àwọn tókù yóò sì jẹ́ àgbàlọ̀ | wikipedia | yo |
Lọ́pọ̀ ìgbà, àlọ́ àpamọ́ ló kọ́kọ́ ma ń wáyé kí wọ́n tó pálọ̀ àpagbé.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí apálọ bá ti pálọ̀ rẹ̀ tán, yóo bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ tí olukuluku rí kọ́,dìmú ninu àlọ́ náà.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Ìlú tọ́pọ̀ jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní eré-kúbẹ́ agbègbè ìlú àgbàdárìgì ní Ìpínlẹ̀ Èkó, bákan náà ni ìlú tópọ̀ jẹ́ ibi tí àwọn ajíyìn rere Ara Ara gbìn agbọ̀n sì ní ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 1845, ibẹ̀ náà sì ni wọ́n kọ́kọ́ dá ilé ẹ̀kọ́ àwọn olùkọ́ sí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Fìlà aṣọ Òfì (Aṣọ-Òkè)Ẹ̀yà fìlà tómi rírọ̀ jẹ́ fìlà Yorùbá tí wọ́n ń fi aṣọ òfì hùnhùn ṣe,òwú àrán tàbí daMáàsì.Nínú èdè Yorùbá irú rẹ̀ ni wọ́n ń pè ní Fìlà.Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé Oòrírun fìlà ní Nàìjíríà,ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkùnrin ni wọ́n ń wò ó nínú ìran aláwọ̀ dúdú.Ìmọ̀lára òkè fìlà gígé sí ẹ̀gbẹ́ kan ni,ìyókù a sì tayọ etí ẹni tí ó dẹ ẹ́ sókè.Àwọn kan sọ pé gígé fìlà sí apá ọ̀tún ń tọ́ka sí àpọ́n kùnrin nígbà tí ẹgbẹ́ oṣì ń ṣàfihàn ọkùnrin tí ó ti níyàwó.Wọ́n máa ń sáábà wò ó pẹ̀lú aṣọ ìmúròde Yorùbá Agbada(ṣe bákan náà pẹ̀lú aṣọ òfì,ẹ̀sì tàbí aṣọ olówùú)tàbí dàńṣíkí tí wọ́n fi aṣọ ṣẹ̀dá ṣe tí ó máa ń ní àwòrán lára.Púpọ̀ nínú àwọn ọkùnrin máa ń wọ fìlà bí i àkẹtẹ̀ pẹ̀lú aṣọ léẹ́ dàńṣíkí.Síbẹ̀síbẹ̀ fìlà aṣọ òfì ara aládé fìlà fìlà kú ni ó gbajúmọ̀ fún yíyan tí a bá ń wọ aṣọ ìmúròde mìíràn.Àwọn obìrin náà kọ gbẹ̀hìn tó bá dé bi kádé fìlà, wọ́n sábà máa fi rán àkéte tàbí dé irúfẹ́ ti ọkùnrin.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì úné fẹ́ràn àti ṣeé ní èso lọ́pọ̀lọpọ̀ pẹ̀lúu gíláàsì bí òkúta kékèèké aláwọ̀ oríṣiríṣi tàbí, ìlẹ̀kẹ̀... | wikipedia | yo |
Ile-ise Amerika ti Brasil ni orisun ti o je pataki ti ilana isakoso fáìlì (sìgá) ni ilu Brasil.. | wikipedia | yo |
O ṣẹda ni ọjọ 2 Oṣu Kínní ọdun 1838 ati pe o ni ori ile-iṣẹ rẹ ni Rio de Janeiro.. | wikipedia | yo |
Gẹgẹbi ofin ti ile-itọju (ofin 8.159) ti Oṣu Keje 8, 1991, o ni ojuse lati ṣeto, tọju, tọju, fun wiwọle ati ki o ṣalaye ohun-ini itan ijọba ti ijọba apapọ, ṣiṣe si ipinlẹ ati awọn ilu.. | wikipedia | yo |
Àwọn gbígba ti ilé-ìpamọ́ ilé-èdè ni 55km ti àwọn ìwé ọ̀rọ̀ ọrọ̀; àwọn àwòrán àti àwọn ìdíyelé 2, 000;000; 27,000 àwọn àpèjúwe, àwọn àwòrán ẹ̀fẹ̀; 75,000 àwọn máàpù àti àwọn ètò; àwọn ìdánilójú àwọn ohun ìtànná tí ó ṣe ìwọ̀n lọ́dọ̀; 90,000 àwọn àwòrán tí a fi ń ṣàwárí àti àwọn àwọn fídíò fídíò 12,000.. | wikipedia | yo |
O tun ni Ile-ikawe ti o ni imọran ninu itan, awọn akọsilẹ, Imọ-ijinlẹ Alaye, Ofin Isakoso ati ìtọ́nisọ́nà Gbogbo Eniyan, pẹlu Awọn iwe ati Awọn iwe 43,000, Awọn iwe iroyin 900 ati Awọn iṣẹ onigbọwọ 6,300.itọkasi.. | wikipedia | yo |
Sori Cole ti àpèjẹ rẹ n jẹ oluṣọji Henry Cole jẹ onkọwe , oṣere, adari ere itage ati sinima ọmọ orilẹ edè Naijiria.Wọn bi oluṣọji Henry Cole ni ọjọ ketadinlogun oṣu ọpẹ, ọdun 1976 ni opopona kokà ni ilu Mushin ni ipinlẹ Eko.. | wikipedia | yo |
Ọ̀mọ̀wé Cole gba ẹ̀bùn Nigeria prize for Literature ti ọdun 2018.eto ẹkọ rẹsoji bẹrẹ ẹkọ rẹ ni Ile-ẹkọ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ St.. | wikipedia | yo |
Micheal ti olôòsa, tí ó sì parí rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àgọ́ òwú ní Sogúnlẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí ni ó tẹ̀ síwájú ní ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Ikeja, tí ó wà ní ọ̀ṣọ́di, ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ewu tún-tún tí ó wà ní Mafolúkúku ní ìpínlẹ̀ Èkó àti iké-ẹ̀kọ́ Girama Orímọlade ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe (uí) ti ìlú Ìbàdàn níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gbàwé ẹ̀rí dípúlómà, gboyè akoko (B.A) ní ọdún 2006, gboyè eleekeji (M.A) ní ọdún 2010, àti oye omowe (PhD) ní ọdún 2016 nínu ìmọ̀ eré orí ìtàgé "Theatre Arts" | wikipedia | yo |
Ti o si n sise gege bi oluko ati adari fun ipele apileko ere ori itage ere onise Abawùjọ mu ni agbon Theatre Arts ti Ile-ẹkọ gbogbo-nise ti ilu Ibadan, nibi ti o ti ko opolopo apileko fun sise ni ori pepe, nigba-máwòrán, ati opo sinima to ti dagbelewo.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, ó tún jẹ́ olùdarí fún eré ìtàgé àti sinimá, bákan náà ni ó tún jẹ́ òṣèré orí ìtàgé.. | wikipedia | yo |
Nínú ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ yí lọ ti gba àwọn ètò ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ àti àwọn àmì ẹ̀yẹ Looriṣiriṣi.Àwọn àmì ẹ̀yẹ tó ti gbàò gba àmì ẹ̀yẹ akẹ́kọ̀ọ́-jáde tó pegede jùlọ ní ọdún 2006, ní agbọ̀n ẹ̀kọ́ òṣèré orí ìtàgé ìgún ( Theatre Arts) ní UI, ó jáwé olúborí tí ó sì gbàmí ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́ tó mọ́ ìtàn eré orí ìtàgé kọ jùlọ jùlọ nínú ìdíje Zulu ṣòjá ní agbọ̀n ẹ̀kọ́ Theatre Atrs bákan náà ní ọdún 2006.. | wikipedia | yo |
Oun lo gba ipo akọkọ ninu idije African Theatre Association, (AFTATA) ti o si gba ami eye Scholars ní ọdún 2011.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, kò dúró níbẹ̀, ó tún gba àmì ẹ̀yẹ oníjí tuntun ( New Scholar) láti ọ̀dọ (ifún/rt) tí ó túmọ̀ sí International Federation for Theatre Research látàrí iṣẹ́ iwadi rẹ̀ tó pegedé ní ọdún 2013.. | wikipedia | yo |
Bakan naa lo tun janfani eto Eko ọfẹ (Diversity Studies International Teaching and Bapeliship Network Fellowship) lati ọdọ fasiti Carl von Ossitz univeveamíty ti o wa ni Olcreating ni orile ede Jamani ni ọdun 2013.. | wikipedia | yo |