cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Ó díje nínú ìdíje FIFA Women's World Cup ti ọdún 2007 ..
wikipedia
yo
Ní ìpele ẹgbẹ́, ó ṣeré fún Ghatel Ladies ní Ghana.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ ará Ghana..
wikipedia
yo
Kulu Yahaya tí a bí ní ọjọ́ kẹtàlélógún osù kaàrún ọdún 1976 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède Ghana tí ó gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí olùgbèjà fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti obìnrin Ghana ..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ó kópa ní bi FIFA World Cup Women's World Cup ti ọdún 1999 ..
wikipedia
yo
lórí ìpele ẹgbẹ́ ó ṣeré fún dáasíwáAman Ladies ní Ghana.Àwọn ìtọ́kasí sí ìta àwọn ènìyàn aláàyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1976..
wikipedia
yo
Sherifatu Sumaila tí a bí ní ọgbọ̀n ọjọ́ Oṣù kọkànlá ọdún 1996 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-ède Ghana kan tí ó ń ṣeré bíi agbábọ́ọ̀lù ìkọlù olùgbèjà àti olùkọlù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Primera Federación Spanish Rayo Vallecano ..
wikipedia
yo
Ó ṣeré tẹ́lẹ̀ fún DJuJudens if Fotboll (àwọn obìnrin) ..
wikipedia
yo
ó tún jẹ́ agbábọ́ọ̀lù tẹ́lẹ̀ fún ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ti àwọn obìnrin United United States, LA Galaxy Orange County ..
wikipedia
yo
Sherifatu jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède Ghana , Black Queens.Eko Sherifatu jáde ní ilé-ìwé gíga feather River Community ní Quincy, California.Àwọn Ìtọ́kasíita ìjápọ Sherifatu Sumaila ní BfutBolBol Sherifatu Sumaila profaili ní ẹgbẹ́ bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá Sweden (in Swedish)àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1996..
wikipedia
yo
Suzzy Dede Teye tí a bí ní ọjọ́ kẹfà Oṣù kọkànlá ọdún 2002 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-ède Ghana kan, tí ó dúró bí aláwà ní orí pápá fún Hatayspor ní Super League ti Turkey àti ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù obìnrin Ghana .iṣẹ́ ẹgbẹ́ Teye gbábọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Premier League Women's Ghana Lady Strikers FC ..
wikipedia
yo
ní ọdún 2021, wọ́n fun ní orúkọ “Player of the Month February”
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kẹẹ̀wá ọdún 2022, ó kó lọ sí Turkey, ó sì buwọ́ lùlù pẹ̀lú Hatayspor láti gbábọ́ọ̀lù ní 2022-23 Sper League .iṣẹ́ òkè-òkun wọn gbà Teye wọlé sínú ẹgbẹ́ U-17 àwọn ọmọbìrin Ghana láti ṣe eré ní bí bí [[2018 African U-17 Women's World Cup qualisting Tournament àti 2018 FIFA U-17 Women's World Cup ..
wikipedia
yo
ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ ti U-20 ti obìnrin Ghana ni bi FIFA U-20 World Cup Women ti ọdún 2022..
wikipedia
yo
Faiza Ibrahim tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún osù kẹta ọdún 1990 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti orílẹ̀-ède Ghana..
wikipedia
yo
Ó gbá bọ́ọ̀lù ní ipò iwájú.Ó mi àwọ́n ní bí ayò mẹ́ta sí odò pẹ́lú Mali ní bí ìdíje àwọn obìrin Áfíríkà ti ọdún 2012..
wikipedia
yo
ó mi àwọn ní bí ayọ̀ mẹ́ta sí odò pẹ̀lú Etiopia ní bí ìdíje àwọn obìrin Áfíríkà ti ọdún 2014..
wikipedia
yo
ó wà nínú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Ghana fún ìdíje àwọn obìnrin fún ọdún 2014 ..
wikipedia
yo
ó kúrò nínú ẹgbẹ́ ti ilẹ̀ Ghana ní oṣù keje ọdún 2015 nítorí pé ó ní ìpalára..
wikipedia
yo
Ó wà nínú àwọn tí ó kópa ní Ghana fún àwọn eré Áfíríkà ti ọdún 2015.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1990..
wikipedia
yo
Rumanatu Tahiru tí a bí ní ọjọ́ kẹrin Oṣù Kẹfà Ọdún 1984 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀-ède Ghana tí ó ṣeré lókè-òkun tí ó mú ipò iwájú lórí pápá..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìrin orílẹ̀-ède Ghana..
wikipedia
yo
Ó wà lára àwọn tí ó kópa ní bi FIFA Women's World Cup ti ọdún 2007 ..
wikipedia
yo
Lórí ìpele ẹgbẹ́ ó ṣeré fún Athlẹ́tà Ladies ní Ghana.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1984..
wikipedia
yo
Ayọ̀ Ayọ̀ọlá-amalè jẹ́ akéwì àti agbẹjọ́rò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríààìpilẹ̀ àti ẹ̀kọ́ rẹ̀wọ́n bí ayọ̀ Ayọ̀ọlá-amalé sí ìlú Jóṣ, Nàìjíríà.Ó dára pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ Peace Movement nígbà tí ó ṣì jẹ́ ọmọdé, ó sì di adarí ẹgbẹ́ Rotaract Club àti Girls Guide nígbà tí ó ṣì jẹ́ ọ̀dọ̀ ọmọbìnrin, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹgbẹ́ obìnrin tí wọ́n dá kalẹ̀ nígbà náà jẹ́ ẹgbẹ́ tí wọ́n dá kalẹ̀ láti tako rírẹ̀ àwọn obìnrin jẹ àti láti tako àwọn ìwà àìtọ́ míràn sí obìnrin..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ Rotary Club ati women in Nigeria(win).baba re, eni ti o kawe gboye ni Yunifasiti ti London, jẹ agbejoro ati oṣiṣẹ elétò abo National security adviser, eni ti o n gba igba keji Aare ni iyanju lori ọrọ eto abo ati Alaga State security Service..
wikipedia
yo
O gba ọpọlọpọ ẹyẹ, pẹlu awọn ẹyẹ miran lati orilẹ-ede Amẹrika..
wikipedia
yo
Ìyà ayò jẹ́ ọmọ ọba, iṣẹ́ ọwọ́ sì ni ó ń ṣe.Ó lọ ilé ìwé St Louis Secondary School, bomPáì, ní Ìpínlẹ̀ Kano fún ẹ̀kọ́ primari rẹ̀ó padà kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní Yunifásítì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, wọ́n sì pè sínú iṣẹ́ òfin ní 1993..
wikipedia
yo
Ó padà tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Yunifásítì ìlú Èkó àti Yunifásítì ti Ghana.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Arabinrin naa ti kopa ninu ere idije ti Marathon fun 1500 metres.igbesi aye elere idaraya naaAbẹ́ùn-ssse ni a bi si Addis Ababa, Ethiopia..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2011, oṣù February, Elvan fẹ́ olólùfẹ́ rẹ̀ ìgbà pípẹ́ tórúkọ rẹ̀ ń jẹ́ SemeNeh Debélìe..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2011, Oṣu July arabinrin naa bimọ obinrin, ti wọn sọ ni arṢema.Ni ọdun 1999, Elvan kopa ninu idije Ikòrí Cross ti Agbaye fun Awọn oje wẹ́wẹ́ ti Ile Ethiopia ni Belfast, Northern Ireland nibi to ti pari pẹlu ipo Kẹsán-an..
wikipedia
yo
Ni ere ti EverGood Bergen BisLett Games to waye ni Norway, osu June, ni odun 2004 abecreatings yege ninu record agbaye awon obinrin ti 5000m..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, abẹyíkássse gba Wúrà ní Marathon ti 10,000m nínú ìdíje ti eré-ìdárayá ti orílẹ̀-èdè Ethiópíà níbi tí arábìnrin náà ti parí pẹ̀lú ọgbọ̀n ìṣẹ́jú lé ní ẹyọ̀kan, ìṣẹ́jú aaya tí 10.23.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
arinọla Olasumbọ̀ Cheya (ti a bi ni ọdun 1953) jẹ ojogbon ni Yunifasiti ilu Ibadan ati Komisona fun Eto-Ilera ara ti Ipinle Oyo, orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Erinola di ojogbon ni odun 2000, eyi ti o so di obinrin akoko lati di ojogbon ninu bi a se n da ise ara bo sipo (ìkọ̀sẹ̀kas.[Therapy) ni orile Afrika, ati obinrin akoko lati di ojogbon ninu imo ṣàríwísíwon ni Naijiria..
wikipedia
yo
O wa lara awon eni iyi ni IpinleOyo.Ola-Irinola ni igba keji adari Yunifasiti iluIbadan..
wikipedia
yo
Earinọlá bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ ni Salvation Army Primary School ní Surulere ti Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
O tẹsiwaju ni Queens College, Yaba, Ipinle Eko nibi ti won ti fi joye head girl..
wikipedia
yo
O kẹkọọ nipa imọ kókóokas ni Yunifasiti ilu Ibadan.Igbe ìjọbaarinola di Komisona fun eto-ilera ara ti Ipinle Oyo, orile-ede Naijiria ni odun 2005.Oko ojogbon sanya ni Dr..
wikipedia
yo
Yemi Cheya, Onimọ ogun òyìnbó ati onisowo ni Ipinle Eko, Naijiria..
wikipedia
yo
EjGaye Taye ni a bini ojo kewa, osu February, odun 2000 je elere idaraya ti ona jinjin ti orile ede Ethiopia..
wikipedia
yo
Taye naa gba ami ọlá ti idẹ fun 3000 metres ti idije agbaye ti inu ile to waye ni odun 2022.Ni osu July odun 2018, EfuGayehu Taye gba ami ọlá ti ninu idije U20 IAAF agbaye ti 5000 metres.Ni odun 2019, Taye gbe ipo karun ninu ere ile afizko ti 5000.itọkasi..
wikipedia
yo
Samuel Adeṣina Gbadebo, eyi ti a tun mọ si Gbadebo II jẹ ọba ni orilẹ-ede Naijiria ti o di oye Aláké ti ilu Egba mu..
wikipedia
yo
Ṣaaju ki o to di aṣalẹ, Gbadebo ṣe awọn ẹtọ ni iwọ-oorun Naijiria lati polongo iṣẹ agbe.igbesi aye rẹ a bi Gbadebo ni oṣu Kẹsán-an ọdun 1908 si idile ọba Gbadebo i ati Esther Omolara..
wikipedia
yo
O di ojogbon laarin Egba Native Authority, nibi ti o ti ni anfaani lati sise pelu Aláké laDapo Ademola, eni ti o ni fe si ise re..
wikipedia
yo
Lẹ́hìn náà, ó darapọ̀ mọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ti ilé-iṣẹ́ Railway Nigeria gẹ́gẹ́ bi akọ̀wé, Ó tún ṣiṣẹ́ ní ojú-irin agbègbè ila-oòrùn àti ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ní ọdún1936, ó padà sí Abeokuta, ó n ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn aláṣẹ Ẹ̀gbá(Egba Native Authority)..
wikipedia
yo
Ó kọ́ ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ ìgblẹdúnúpó) ní Ìbàdàn, ó sì di olórí àwọn tí ń rí sí ọ̀rọ̀ Igbó ní Ẹ̀gbá..
wikipedia
yo
Laarin odun 1954 si 1955, o kẹkọọ ni British forSty Commission..
wikipedia
yo
Nigbati o pada si Naijiria, o ṣiṣẹ fun agbegbe iwọ-oorun Naijiria ni ṣiṣe ifihan iṣẹ-ogbin.Ni ọdun 1963, wọn fi jẹ oye Aláké ti ilẹ̀ Ẹ̀gbá..
wikipedia
yo
Awon igbimo naa a ma fi ìpinu won ranse si igbimo agbegbe Abeokuta..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó gbé ìgbìmọ̀ ìṣọ̀kan kan dìde láti ṣàkóso àwọn ọ̀ràn ti ìgbìmọ̀ agbègbè..
wikipedia
yo
O sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ ńná Akintola nígbà tí wàhálà òṣèlú ṣẹlẹ̀ ní ìwọ̀ oòrùn ní láàrín ọdún 1964 sí 1966, ó sì fẹ́ bèrè fún àtìléyìn wọn fún ilẹ̀ Ẹ̀gbá.Ọdún 1971 lo papòdà, Ọba Lipèdè ni ó rọ́pò rẹ̀..
wikipedia
yo
Òun jẹ́ àbúrò ọ̀kan lára àwọn òbí ọba Gbádébọ̀ III.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Serkalem biset Abrha ni a bí ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù March, ọdún 1987..
wikipedia
yo
Arabinrin naa jẹ asare to wa lati orile-ede Ethiopia to si tun kopa ninu orisirisi idije ona jinjin.igbesi aye bisetbiset ko ise ere-sísá pelu bizuntọ̀túntòsì débá, Genna Tufa, ati Atalelech asfaw ni ile New York ati Albuquerque, New Mexico..
wikipedia
yo
Ara iṣẹ́ arábìnrin náà ni eré-sísá lọ sí orí-òkè Addis Ababa, Ethiopia pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ nínú eré-sísá.Ère-sísá-sísá Abrha àkọ́kọ́ ní ìta orílẹ̀-èdè Ethiopia wáyé ní ilẹ̀ India ní Delhi àti Lahore 10k láti ọdún 2005 dé ọdún 2007..
wikipedia
yo
Abrha parí pẹ̀lú ipò kejì nínú ìdájí Marathon ní ọdún 2006 níbi tó ti gba owó ẹgbẹ̀rún Dollar..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2008, Abrha yege nínú Maas Marathon tó wáyé ní vise, Belgium..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2009, arábìnrin náà kópa nínú Atlanta Marathon ní Georgia níbi tó ti ṣáájú àwọn obìnrin tó sì gba ẹ̀bùn ẹgbẹ̀rún mẹ́ta Dollar..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010, arábìnrin náà parí pẹ̀lú ipò kẹta nínú Marathon ti Las Vegas níbi tó ti gba owó ẹgbẹ̀já mẹ́rin Dollar..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2011, Abrha yege nínú Marathon ti California tó wáyé ní Sacramento, California..
wikipedia
yo
NetSanet Achamo ti a bi ni ojo kerinla, osu December, odun 1987 je elere ṣíṣá ona jinjin ti orile-ede Ethiopia.aṣeyorinetetet pari pelu ipo kerin ninu idije awon elere ni odun 2006 ni 3000 metres..
wikipedia
yo
Achamo kópa nínú ìdíje àgbáyé ti eré-sisá nínú 300 metres ti Nebukadinésárìplechase ní ọdún 2007..
wikipedia
yo
Arábìnrin náà gba idẹ nínu eré gbogbo ilé Afiko ti ọdún 2007 lórí 3000 metres ti Kérésìmesìplechase..
wikipedia
yo
Achamo yege ninu idaji ọlọ́mọUC Marathon ni ọdun 2011, Mumbai Marathon ti ọdun 2012 ati Hamburg Marathon ti ọdun 2012.Àwọn itọkasi..
wikipedia
yo
Kate Adébọ́lá òkìkí (tí a bí ní ọdún 1965) jẹ́ onísin Máàsì, ọmọ orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan..
wikipedia
yo
Awon eniyan mo on fun ise re pelu Elliptic differential operators ati inner-city Children.ipilẹ aye ati Eko rea bi okikiolu ni 1965 ni England..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ ní George Olatokunbo òkìkí, ó jẹ́ onímọ̀ mátì tó gbajúmọ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan tí ó ń kọ́ mátì ní ilé-ẹ̀kọ́ kan..
wikipedia
yo
Ninu imo mátì ni Yunifasiti ti Cambridge ni odun 1987..
wikipedia
yo
Ninu imo mátì ni Yunifasiti California ni Los Angeles.àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Ìtàn àròsọ Yorùbá mú wa gbàgbọ́ pé àwọ Òwu tẹ̀dó sí agbègbè kan tààrà lẹ́ẹ̀bá odò odò Ọya ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Olowu ti ilu Owu je oba Alade ilu Owu.Àwọn Ọmọọba tí wọ́n yàn láti ìdílé ọba mẹ́fà tí n ṣe; Amororo, Otileta, Ayoloye, Akínjobi, Akinoso àti Lagbedu ló ń darí ìlú Òwu..
wikipedia
yo
Àwọn Ògbóni àti àwọn ológun ló máa ń ran ọba lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Balógun ló jẹ́ olórí àwọn ìjòyè, lábẹ́ rẹ̀ ni a sì rí Otun, Osi, Seriki, Ààrẹ Ago àti Jagunna..
wikipedia
yo
Lára àwọn olóyè Ògbóni ni Akọgun, ỌbaMaja, Orunto, Oyega, osuàgbààgbà ati Ovsin..
wikipedia
yo
Láti ipile, ilu Owu ni ìletò meta, ti ń se yun Owu, Erunmu ati Apomu..
wikipedia
yo
Nínú ìṣẹ̀ṣe, àwọn afọbajẹ mẹ́fà ló máa ń yan Olowu, amo wọ́n ti fi olóyè méjì kún un ní ọdún 1964, tí ń ṣe Balogun àti Olosi.Àṣà Ògbóni ó sí lára àwọn àṣà ará ìlú Owu tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Ọwọ́ àwọn Ẹ̀gbá ni wọ́n ti ya, lẹ́yìn tí àwọn Òwu tẹ̀dó sí ìlú Abeokuta..
wikipedia
yo
Èyí sì ni ìdí tí àwọn Owu ò ní Ilédì (ilé Ògbóni) títí ní.Ní ọdún 2006, lábẹ́ àsìkò ìjọba Olowu, Ọba Olusanya Adegboyega Dosunmu (ama II), wọ́n ṣàtò ètò ìṣèlú..
wikipedia
yo
Wọ́n tún ètò ìṣèjọba Ògbóni àti ológun tò, wọ́n sì yan ìgbìmọ̀ tuntun tí a máa ṣe ìjọba..
wikipedia
yo
Saka Adelola Matemilola Olùyalo Otileta VII láti ọdún 2022 - títí ní (OTILETA Family)àwọn Ìtọ́kasí àwọn ỌBA àti ìjòyè ní Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Articles with HcardSabgella-Azeez Olajide Adediran tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Jandor, jẹ́ olóṣèlú Nàìjíríà, Oniroyin, onisowo ati Onimọ-ẹrọ..
wikipedia
yo
Oun ni Alaga ẹgbẹ Lagos4Lagos ati oludije ipo gomina ipinlẹ Eko labẹ ẹgbẹ oṣelu People's Democratic Party pẹlu oludije ati Igbakeji rẹ, Funke Akindele ..
wikipedia
yo
Ó gba Doctorate Honorary nínú ètò ìdarí àti ìṣèjọba ní South American University, ní ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà.Igbesi ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ a bí Jandor sí ìdílé Alhaji Adeniran àti olóògbé Ruth Oluwafunmilayo ní ọjọ́ ní ọjọ́rún Oṣù kọkànlá ọdún 1977 ní agbègbè Mushin ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Jandor jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́-gboyè láti ilé-ìwé gíga ti Polytechnic ti ìlú Ìbàdàn, Modul University, Vienna, Howard University School of Business, Washington DC, ní orílẹ̀ èdè America àti Oxford University, United Kingdom .Iṣẹ́ rẹ̀ Jandor bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú iṣẹ́-ìròyìn, tí ó sì jẹ́ akọ̀ròyìn fún bíi ogún ọdún..
wikipedia
yo
Òun ni olùsẹ̀sí ìgbìmọ̀ ti Lagos4Lagos, ẹgbẹ́ kan lálà APC..
wikipedia
yo
Níkẹyìn, ó padà lọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ PDP, ó sì jẹ́ olùdíje ipò gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó tó kọjá.Àyè rẹ̀ Maryam Olajide Adediran ni ìyàwó rẹ̀, wọ́n sì bí ọmọ méjì; CONEedah Oluwata Amoke àti FTIF|lah Olúwamúrewa Adedayo Akanniade Olajide-Adediran.Àwọn Ìtọ́kasí Ìpínlẹ̀ Èkóàwọn olóṣèlú ará Nàìjíríààwọn Ọjọ́ìbí ní 1977àwọn Ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Akọ̀ròyìn jẹ́ ẹni tí iṣẹ́ rẹ̀ ní ṣe pẹ̀lú gbígba ìròyìn (yálà ní àkọsílẹ̀ tàbí lórí fọ́nrán, tàbí àwòrán), ṣíṣe àtòjọ àti àtúntò àwọn ìròyìn náà, àti ìpínkárí ìròyìn náà fún àwọn ará-ìlú.Akún dọìyànlis ìtọ́kasí ìṣeròyìn..
wikipedia
yo
A Bolaji Abdullahi Doyin Abiola Olu Aboderin Wale Aboderin Ádámù Adamu Kaoriria Ahmed Taiwo Ajai-cett Àjàlá Travel Kunle Ajibade Levi Chibuike Ajuonuma Laolu Akande Yewi Akinbobola Eniola Akinkuotu Richard Akinnola Kayode Akintemi dídì Akinyelu Henry Henry Aldu Ngozi Alaegbu Molani Àlàkẹ́ Lanre Alfred Duse Mohamed Ali Ikechukwu Amaechi Femi D Amele Sam Amuka-Mu Jahman Anikulapo Kola Muslim Anika Samuel Aruwa pelu Awo Steve Ayorin Ayo Jerry fi Bsáyọ̀ ati Tunji Bello Segun Stephanie Stephanie Buce Robert Robert (Coloce (Coloce Vivian Clinton Abiru Coos Coo Da Da Rocha Mamman Da You Di Stella-Ja Be Chike Frankie tòsí Ezimo E James Angelawa Peterwa Peter Tunde Tunde India Ngozi Ezef Adebayo Fálétí Omo Mo FTV Mi Laroko Fi Nuófó Fi Muhammad Garba Adece Adefàyè Ado tòótọ́ Ka Tuntun Da Hannah Ojo ajakaye Sharu Rena Bíṣọ́ọ̀bù Hamza Chris Chris H N Jaa Jaa Ja John Payne Jackson Lateef Jakande Patricia Patricia kale from FM Simon Kan Sale Kpèrò Mo Lá Capewa Sanru Wa Herbert Macaulay Adewale- ce May Ellen-Damijo Mo M-Ece 20 Momoh The Kìkì Odi O 2016 Mu Tuntun & Bami B..
wikipedia
yo
Abubakar Ngozi Nwozor-Agbo Ijeoma Nwadigwu Mazi nwọnwuo Òtòṣìrie Obi-Young Tolu OgunLesi lola Ògúnnáì OluwaTo Ogunseye Ogechukwukan Oghiwo Malcolm Ohanwe Adekunle Ojora Chris Okolie Ernest Okonkwo Victor Ọládòkun Yusuph Oyelani Dapo Olorun Kolade Dominate Olowu Joshua Olufemi Sam Orit- OYÌN Kemi Omo -lo Gbenga Omotoso Duroso Onabule Ona Bayo on Chido OyO Ruth Okunkun Olusegun Oroko to Miroko O sa'a Ibrahim ch Ibrahim Salals Salals Umar Richard Akin Akinwande Savage Ibrahim Shemet en (2016 tan Kola Tubosunu * * _*Bangka Aruka Uroko Funmi wa Adema AdeWilliams Rotimi Williams African A Olutun Oluce O Gloria Young..
wikipedia
yo
Articles with HcardsGbadebowale Aboderin (1958 – 30 May 2018) jẹ oniroyin lati orile-ede Naijiria, onisowo ati ALÁBÒÓJÚTÓ Ere-idaraya..
wikipedia
yo
Oun ni Alaga iwe-iroyin Punch titi igba to ku, eyi to je ile-iṣẹ ti baba re da sile..
wikipedia
yo
Ìwé-ìròyìn Vanguard ṣe àpèjúwe ìwé-ìròyìn yìí gẹ́gẹ́ bíi òpó kan pàtàkì fún iṣẹ́ ìgbéròyìn jáde..
wikipedia
yo
Ó kàwé ní Government College, ní ìlú Ìbàdàn àti Clífton College, kó tó lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa ọkọ̀ òfurufú ní burnside-Ott flying School..
wikipedia
yo
Ninu ere-idaraya, o jẹ Alaga, ẹgbẹ agbabọọlu agbabọọlu ipinlẹ Eko ati Igbakeji Aare ẹgbẹ agbabọọlu Naijiria..
wikipedia
yo
ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà, Muhammadu Buhari, Gómìnà Èkó tẹ́lẹ̀ rí, Akinwunmi Àmbọ̀dé wà lára àwọn tó ṣàánú fún àwọn ẹbí rẹ̀..
wikipedia
yo
ní ọdún 1997, ó ṣe ìdásílẹ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù inú àpẹrẹ aládàáni ti ilẹ̀ Nàìjíríà àkọ́kọ́ fún àwọn obìnrin, Dolphins.ikú rẹ̀ Wale Aboderin kú ní 30 May 2018 ni Ikoyi, Ìpínlẹ̀ Èkó, ni ẹni ọdún 60.Àwọn ìtọ́kasí àwọn oníròyìn ará Nàìawọn Ọjọ́ìbí ní 1958..
wikipedia
yo
Articles with Hcardskunle Ajibade (tí wọ́n bí ní 28 May 1958) jẹ́ akọ̀ròyìn, olóòtú àti òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo