cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Uwani Musa àbbá Ajigún (tí a bí ní ọjọ́ keje Oṣù kọkànlá ọdún 1956) jẹ́ olùdájọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti olùdájọ́ ilé-ẹjọ́ agbá orílẹ̀-èdè ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àárọ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ kò bí Ajiá ní ọjọ́ keje Oṣù kọkànlá ọdún 1956, ní ìlú Gashua, ìpínlẹ̀ Yobe..
wikipedia
yo
Ó tètè bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé-ìwé Central Primary School Gashua ní ọdún 1961, tí ó sì tẹ ẹ̀kọ́ rẹ̀ síwájú ní Government Girls Secondary School, Maiduguri níbi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí wáEC rẹ̀ ní ọdún 1972..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1976, ó gba àmì-ẹ̀yẹ "diploma in Law" ní Yunifásítì Àmọ́dù Bello ti Zaria ní ọdún 1980, àti àmì-ẹ̀yẹ l.L.B hons ní ilé-ìwé kan náà..
wikipedia
yo
Aji bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òfin ní ọdún 1981.Ìdílé Reuent fẹ́ Musa Ábbà-Aji, àwọn méjéèjì sì bí ọmọ mẹ́ta, Musa jẹ́ ọ̀gá agba Borno state Civil Service tẹ́lẹ̀ ri..
wikipedia
yo
Uwani ni àwọn nǹkan tí òún fẹ́ràn láti má ṣe ni ki kàwé, kí kọ̀wé, kí òun máa rin ìrìn-àjò àti kí ó máa tọ́jú ọgba.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Fadima Murtala Aminu je ọmọbinrin ti a bi ni ojo ogbon osu kerin, odun 1968 ni Zaria, Ipinle Kaduna ni ile Naijiria..
wikipedia
yo
ó jẹ́ adájọ́ pẹ̀lú ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Tóyìn kúbíkú Adédi tí a bí ní ọjọ́ Kẹrìnta, oṣù ogún, ọdún 1964 jẹ́ adájọ́ ilé-ẹjọ́ ìjọba àpapọ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó ka ìwé mẹ́wàá rẹ̀ tán ní ojúkú Grammar School ni ọdún ni ọdún 1981..
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Fásitì Maiduguri, ní ìpínlẹ̀ Maiduguri LỌ́DÚN 1987 láti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ ède gẹ̀ẹ́sì (English).Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mójì ọmọ-À (ọdún 1922 - ọjọ́ karùndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kejì ọdún 2002) jẹ́ àròròó ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ọ̀jọ̀gbọ́n amo tí ó jẹ́ Adájọ́bìnrin àkọ́kọ́ ní orílẹ̀ èdè náà.Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ wọn bí Mokò Akingbẹ̀hìn sí ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1922..
wikipedia
yo
Ìyá rẹ̀ jẹ́ Ọmọ-ọmọbìnrin Oshodi tápá gbajúgbajà l'ẹkọ àti ọmọọmọ-ọmọbìnrin ti Bishop Samuel Àjàyí Crowther, tí òun fúnra rẹ̀ jẹ́ àwọn ọmọ Ọba Abiodun ti Oyo..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Queen's College, ti Èkó kí ó tó lọ kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀-òfin ní ìlú-ọba.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
NkemdiLim Amelia Izuakọ jẹ́ adájọ́-bìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2009, ó ti wà lára ọ̀kan lára àwọn adájọ́ mẹ́ta àkọ́kọ́ ní United Nations dispute Tribùnal (undt).eto-ẹ̀kọ́ rẹ̀ Izuakọ gba kẹ́kọ̀ọ́ níoa òfin, ó sì gba ìwé-ẹ̀rí ẹ̀kọ́ náà ní Obafemi Awolowo University..
wikipedia
yo
O ti sise gege bi oluko imo-ofin ni Nnamdi Azikiwe University ati Gábíàbíà Technical Institute.Iṣẹ re gege bii adajo Izuako di adajo ni ọdun 1998, nigba ti won yan an si ile-ẹjọ ti Ipinle Anambra; won pada yan an si Ile-ẹjọ giga ti Orilẹ-ede Naijiria, o si sin nibẹ titi di ọdun 2003..
wikipedia
yo
Láti ọdún 2004 wo 2006, ó sìn gẹ́gẹ́ bíi adájọ́ ní ilé-ẹjọ́ gíga àti ilé-ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ti orílẹ̀-èdè Gábíàbíà..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2006, wọ́n yàn án sí High Court of Solomon Islands; òun sì ni olùdájọ́bìnrin àkọ́kọ́ tí wọ́n máa kọ́kọ́ yàn sí ilé-ẹjọ́ Solomon Islands.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Kelvin Katey Carbóo ti wọn bi ni ọjọ kẹwàá oṣu Kẹta (Oṣu Erena), ọdun 2000..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ eléré ìlà bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá (Volleyball) tẹ́lẹ̀ ní orílẹ̀-ède Ghana..
wikipedia
yo
.Ìgbésí ayé àti ìṣe rẹwọn bí Carbóo ní ìlú Accra, ní orílẹ̀-èdè Ghana..
wikipedia
yo
Carbóo bẹrẹ iṣẹ rẹ gege bii elere-idaraya Volleyball ni odun 2017, nigba ti o kopa ninu ere Volleyball awon oje wẹ́wẹ́ ninu idije Commonwealth pẹlu Akin ẹgbẹ rẹ Eric tsat, ti wọn si gbe ipo kẹrin ninu idije naa..
wikipedia
yo
Ni osu keje, odun 2018 elere naa kopa ninu ere awon odo ile afitun to waye ni ile Algeria..
wikipedia
yo
Ní Oṣù Kẹfà , Ọdún 2019 arákùnrin náà kópa nínu eré Eti Odò àkọ́kọ́ ilé Afiko pẹ̀lú Akin ẹgbẹ́ rẹ̀ EsSilfíc Samuel Tetteh tí wọ́n sì gba ipò kejì.ní Oṣù Kíníọdún 2020 elere náà kópa nínu ìfẹ́ tí Caibùdó (CAOdi Cup) ní ilẹ̀ Accra pẹ̀lú Akin ẹgbẹ́ rẹ̀ EsSilfífí níbi tí wọ́n ti gbégbá orókè ṣe ipò àkọ́kọ́.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
CenCen Ahiẹyọ ni a bini ọjọ́ kẹtàlá,Oṣù April, ọdún 1945 jẹ́ afẹṣẹja orílẹ̀ èdè Morocco.Àṣeyọrílah kópa nínú Olympics ti Summer ní ọdún 1964 àti 1968.Ìtọ́kasí.
wikipedia
yo
Ayọ̀Tunde Phillips(Chief Justice ti Ipinle Eko lati ọdun 2012-2014) Kudirat kékeré-Ẹkún(adájọ́ Ile-ẹjọ́ to ga julọ ni orilẹ-ede Naijiria) Eberechi Wike Daisy W..
wikipedia
yo
Okocha(Adájọ́ àgbà Keje ti Ìpínlẹ̀ Rivers) Olubunmi Olateru Olagbegi(adajo Agba ti Ipinle Ondo lati odun 2003-2010) Binta Fatima nyako Uche NAM Agomoh Zainab Bagé Abubakar Anwu ICHELA O Chikere Joyce Ohihi Abdulk Tóyìn Wọ̀nyí Adegoke Nehi Odẹ́rùbani Idẹmo Aebimọ Aroko Ojukwu Fma Murtala Aminu Conmi Omowunmi Oguntoyin M.A..A..
wikipedia
yo
Onyete dìza Rabiu Shagari Folashade Adekòké Adéyán OluBanjo Aguv àgatha Okeke Dorcas Veneńgé agishi MoreNike Olabo Owaye Fati lámì Abubakar Mogbo Ọmọ-e Olatokunbo Olóka Uko Musa Ser Aji Monica Dongban-U Raìmọ̀ràn Rdea HakokoJoeàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Morekéjì Ọláfmbọ̀ Ọbadínà (ti wọn bi lọ́jọ́ Kesan-an oṣù Kẹwàá ọdún 1963) jẹ́ Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ Giga Ìjọba-ìpínlẹ̀ Èkó ti ó wà ni Igboṣere ni Nigeria...
wikipedia
yo
Ijọba ipinlẹ Eko yan an gege bi adajo lodun 2001awon itọkasi..
wikipedia
yo
dìgáza dáwàiya Shagari, tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mó sì dìza Shehu Shagari (ọdún 1940/41 – Ọjó kejìlá osù kẹjọ ọdún 2021) jẹ́ gbajúmọ ènìyàn, obìnrin àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà láàrín 1979 tó 1983, àti ìyàwó Shehu Shagari nígbà tí àwọn méjèèjì wà láyé..
wikipedia
yo
Oun ati awon iyawo Shagari to ku je obinrin akoko ile Naijiria nigba ti Shagari je aare ile Naijiria laarin ojo kinni osu kewa odun 1979 si ojo kanlelogbon osu kejila odun 1983.Ìtàn ayé re hadi Dwa pade ọkọ re, Shehu Shagari, ni Ipinle Sokoto..
wikipedia
yo
Wọ́n fẹ́ ara wọn ní ọdún 1957.hadiza Shagari kú nítorí ààrùn COVID-19 ni Gressywalàdá, Abuja ní ago mẹ́ta àárọ̀ ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹjọ ọdún 2021..
wikipedia
yo
Ìsìn kún rẹ̀ wáyé ní Abuja National Mosque ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹjọ ní ago mẹ́rin ọ̀sán..
wikipedia
yo
Oko rẹ̀, Ààrẹ tẹ́lẹ̀rí Shehu Shagari, fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 2018.Àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Mustapha adnane ni a bini ọdún 1931 tó sì kú ní ọjọ́ kejì dínlọ́gbọ̀n, oṣù April, ọdún 2006 jẹ́ àdánù gbígbẹ́ ti orílẹ̀ èdè Morroco.MustaMustapha kópa nínú Olympics Summer ti ọdún 1960 àti 1964.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Vivian Aminu Yusuf ni a bini ọjộ kẹjọ, osù kẹjọ(ogún) ní ọdún 1983, ó jé òkan nínu àwọn obìnrin tó kópa nínu èrè jú ní orílẹ̀ èdè Nàíjírìa nínú abala idaji heavy.[vedkunkunkun gba àmì ọ̀la ti idẹ ní èrè tí gbogbo ilé afiú ní ọdún 2007 tó wáyé ní Algiers àti ìdíje jú ti ilé afiẸ̀mi ní ọdún 2008 tó wáyé ní àgaDir, Morocco.Vivian kópa nínu eré Olympics ti Summer nibi ti arabinrin náà ti sojú na sójú nínu xyäy OLY ní Beijing, China níbi tó ti kópa nínu idaji si idaji (78).
wikipedia
yo
Ijeoma Lucía Ojukwu je ọmọbinrin ti a bi ni ojo kerinla osu kejila odun 1966 ni Kaduna, ni ile Naijiria..
wikipedia
yo
O kọkọ gba atifikeeti oye (WAEC) Akoko rẹ ni ọdun 1985..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ adájọ́ Ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O wa lati Ipinle Abia.aye re arabinrin naa wa lati akuma ni ijoba ibile iwo-oorun Oru ni Ipinle Imo, o si ti je iyawo pelu ojogbon Ernest Ojukwu, San ti o je omo ilu Ikwuato ni Ipinle Abia..
wikipedia
yo
ó sì ti bímọ márùn-ún.Ìrìn àjò iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí adájọ́ onídàjọ́ Ojukwu gbajúgbajà fún bí ó ṣe ṣe ìtọ́jú ẹjọ́ Ọmọyele Sowore, Akọ̀ròyìn Nàìjíríà àti àpéjọ #Revọyọnnnnw àti olùjẹ́jọ́ rẹ̀, oláwálé Bakare, ṣe olórí ilé-ẹjọ́ 5 ní agbègbè Àbújá ti ilé-ẹjọ́ náà.A pè é sí ẹgbẹ́ Adájọ́ (Bar) ní ọdún 1990 àti pé ó ní oyè Máma ní Òfin (LL-Ọ̀-ajo rẹ̀ lórí ibùjókòó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú yíyan rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí alákóso àgbà kejì ní ilé-ìgbìmọ̀ ìdájọ́ ìpínlẹ̀ kan ní oṣù kẹfà ọdún 1996 níbití ó ti ṣiṣẹ́ nípasẹ̀ àwọn ipò títí di oṣù kìíní ọdún 2006 nígbà tí a yàn-án ní Olóyè Karsift ìtẹ́ kìíní.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Zainab Bagé Abubakar jẹ́ adájọ́ ní ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n bi i ní ọjọ́ ọ̀kan-dín-lógún oṣù Kọkànlá ọdún 1964 ní Zuru ní ìlú Kebbi.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Justice Joyce Oọbẹ̀ Abdulmalik je adajọ ni Ile-ẹjọ giga ti Ijoba apapo ti orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
A bí i ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù keje ọdún 1968 ní London, ní ilẹ̀ United Kingdom..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ iwọ-oorun ẹ̀san ní ipinlẹ Edo.àwọn itọka si..
wikipedia
yo
Dorcas Veneńgé agishi (tí a bí ní ọjọ́ kẹjo osù kẹrin ọdún 1961), jẹ́ adájọ́ ilé-ẹjọ́ gíga ti ìjọba àpapọ̀ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó wá láti Ìpínlẹ̀ Benue, àti pé ó jẹ́ ìyàwó sí Solomon agishi tí ó wá jẹ́ ọkọ rẹ̀.Àwọn ìtọ́ka sí..
wikipedia
yo
Beni Lar (ti a bi ni ọjọ kejila oṣu kejo ọdun 1967) jẹ oloselu ọmọ ẹgbẹ People's Democratic Party lati Ipinle Plateau, Naijiria..
wikipedia
yo
O je asoju iko Langtang North ati LangTang South ti Ipinle Plateau ni ile igbimo asofin kekere..
wikipedia
yo
A kọ́kọ́ yàn sí ipò náà ní 2007, wọ́n sì tún dìbò yàn ní ọdún 2019 fún sáà kẹrin ní ipò náà.ÌTÀN AYÉ àti isẹ́ rẹ̀ òun ní ọmọbìnrin àkọ́kọ́ Solomon Lar, Gómìnà ìpínlẹ̀ Plateau Lebíà̀ àti ọ̀jọ̀gbọ́n Mary Lar Lar..
wikipedia
yo
Bẹ̃ni wípé,“Bàbá mi kọ́ mi pé kò sí ìyàtọ̀ láàrín ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin..
wikipedia
yo
Ó kọ́ mi láti jẹ́ oníṣẹ́ takuntakun; nítorí náà, mo gbìyànjú láti jẹ́ agbẹjọ́rò bí bàbá mi.“Ó gba àwọn ọmọ Nàìjíríà níyànjú láti má gbàgbé iṣẹ́ takuntakun tí bàbá rẹ̀ ṣe láti mú ìṣọ̀kan, àlááfíà àti ìfẹ́ wá, ó ní pé àwọn nkan yìí jẹ́ àwọn nkan tí ó ṣe pàtàkì láti mú kí Nàìjíríà tẹ̀ síwájú.Ní ọdún 2007, a dìbò yàn sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2008, ilé Ìgbìmọ̀ asòfin yàn gẹ́gẹ́ bi alága ilé Ìgbìmọ̀ asòfin kékeré lórí ọ̀rọ̀ obìnrin., ó jẹ́ aṣojú ikọ̀ LangTang North àti South..
wikipedia
yo
O tun jẹ Alaga ile igbimọ aṣofin lori ọrọ eto eniyan.O fowo si fifi owo ran aájò National Agency for the Prohibition of Trafficking in Persons (NAPTIP) lọwọ, fifi ọwọ lile ofin mu awọn ti o n ba ọmọde ṣe nkan aito ati dida ààjọ National Child Protection and Encement Agency kalè.Awon Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Abdelhak Achik (ti a bi ni ọjọ Kọkànlá, oṣu Kẹta ọdun 1959) jẹ afẹṣẹja orilẹ-ede Morocco igba kan ri..
wikipedia
yo
afẹṣẹja naa gba ami ọla ti idẹ ni Olympic ti Summer to waye ni Seoul.AbdelAbdelhak kopa ninu ere Olympic ti ọdun 1988otoaye eini Seouni round 64, 32, 16, Quarterfinaa ati semifinalini II o o ti gbàmí i ala ti idẹ.Awon itọkasiawọn ara Mòrókò..
wikipedia
yo
Eedọ Doudou ni a bini ojo keji, osu kerin (April), odun 1959 ti inagijẹ re nje Okazts A-ko-ni-Mo-ni-O-gba (coach) ere bọọlu aláfẹsẹ̀gbá ati elere tẹlẹ ri to ṣere gegebi Agbile (Gofara) orile ede Morocco.Iṣẹ Eedrírán ṣoju as sale, WyDad AC, CRC Marúdurùduca ati Fth Union gegebi elere bọọlu aláfẹsẹ̀gbá..
wikipedia
yo
Arákùnrin náà kópa nínu ìfẹ́ ẹ̀yẹ eré Bólú orílẹ̀-èdè Àgbáyé tí a mọ̀ sí FIFA Cup ti ọdún 1986 àti ìfẹ́ ẹ̀yẹ orílẹ̀-èdè Afiko tí a mọ̀ sí African Cup of Nation lẹ́ẹ̀mẹ́rin.Ní ọdún 1986, Eedst ni a ó ní elere bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ti ilé Afiko lẹ́yìn náà ní elere náà yege nínú La Liga ní ọdún 1989 níbi tó ti gba ìfẹ́ ẹ̀yẹ ti Ricardo Zamora.ew gba elere tó pegede jùlọ ní orílẹ̀ èdè Morocco ní ọdún 1979, 1981, 1986 àti 1988.ní ọdún 1986, Eedst jẹ elere bọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá CAF ti ilé Afiricaniani ọdún 2017, bádou jẹ́ coach tó pegede jùlọ ní ìlú Algeria.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Catherine Obianuju Acholonu (ti a bi ni ojo kerindinlogun osu kewa odun 1951 - ojo mejidinlogun osu keta odun 2014) je Olùkọ̀wé, oloselu ati ajafeto eni omo orile-ede Naijiria.Oun ni Senior Special adviser (ssa) si Aare Olusegun Obasanjo lori oro aworan ati asa, o si tun je omo egbe Association of Nigerian authors (ana).ipilẹ ati eko re a bi Catherine sinu idile Chief Noárua Emewe Olumbamba ati Josephine Olumba, ni Umuwàrà village, ti ilu Orlu..
wikipedia
yo
Oun ni akobi ninu awon omo merin.O pari eko primari ati sekondiri re ni ile-iwe Holy Rosary School, ki won to fe fun Brendan Douglas Acholonu nigba ti ,o je omo odun metadinlogun, Douglas je onise abe, orile-ede Jemani si lo kale si nigba naa.Ni odun 1974, Catherine te eko re siwaju ni Yunifasiti ti Düsseldorf, o si kẹkọọ gboye ni ile-iwe naa lodun 1977..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1982, ó gba àmì-ẹ̀yẹ PhD nínú ìmọ̀ ède igbó.IKÚ Reacholonunu fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kejìdínlógún Oṣù Kẹta 2014, ó jẹ́ ọmọ ọdún méjìlélọ́gọ́ta nígbà náà, ó kú látàrí àìsàn kíndìnrín.àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
BilKisu Yusuf, tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí Haijìyà Bilderick Yusuf, (Ọjọ́ Kejì Oṣù kejìlá Ọdún 1952 - Ọjọ́ Kẹrìnlélógún Oṣù Kesan 2015), jẹ́ oníròyìn àti akọ̀ròyìn fún àwọn ilé ìròyìn tó gbájúmọ́ ní Abuja, Kano àti Kàdúná, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ooredà jẹ́ ẹ̀yà ọmọ Yorùbá máa mọ̀ Hausa, Mùsùlùmí, àti ajàfẹ́tọ́ obìnrin, òun ni ó ń gba Ààrẹ ní imọran lóri àwọn ọ̀rọ̀ tó bá pa Nàìjíríà papọ̀ mọ́ òkè òkun àti nípa dídá àwọn ààjọ tí kò sí lábẹ ìwà ìjọba kalẹ̀, àwọn Ààjọ bi Women in Nigeria (win) àti The Federation of Muslim Women's Association (Fopala)..
wikipedia
yo
Yusuf fi ayé sílẹ̀ látàrí ìtẹpa 2015 mina Stampede nigba ti o wa ni àwọ̀np ni Mecca, Saudi Arabia.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn oníroyìn ará Naijiriàwọn oniroyin ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
{|date=2 July 1968}}↑ termstart = 2003| term = 2009}} Magistrate Folashade Adekòké Adeyán OluBanjo (ọjọ́ ìbí jẹ́ ọjọ́ kejì osù keje, odún 1968) jẹ́ adájọ́ àgbà tí wọ́n bí sí ìpínlẹ̀ Katwo ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó sì ṣe ìsìn fún ìjọba láti óò kini oṣù kẹjọ ọdún 2003 tí di ọdún 2009.Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbé AyéFolashade tí wọ́n bí sí ìlú Katn jẹ ọmọ ìpínlẹ̀ Oyo, tí ó lọ sí ilé ìwé alakọbẹrẹ ti Fásitì Ìbàdàn tí wọ́n pè ní University of Ìbàdàn Senior Staff School ní ọdún 1972 sí 1978..
wikipedia
yo
Ti o si lọ si ile iwe sekondiri Queen's School ni Apata ni Ilu Ibadan ni ọdun 1978 si ọdun 1983, leyin ti o kuro ni 1983 ni Queen's School ni o se bẹẹ o lọ si International School ti Fasiti ilu Ibadan ni ọdun 1983 si ọdun 1985..
wikipedia
yo
Folashade kawe gboye ni ile eko giga lori iṣẹ ofin ni Fasiti ilu Ibadan ni 1985 si 1988, bi ko sai maa lọ si Nigerian Law school ti o wa ni Victoria Island ni Ilu Eko lati 1988 si 1989.Iṣẹline jẹ Agbẹjọro ati Barrister ninu ofin ti o si gboye 2nd class upper pẹlu oye ọla (Division Honours) ni ọdun 1989, eyi ti o si bẹrẹ si ni sise ni ọdun 1990..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1990, Oṣù kejì ọdún náà sí Oṣù Kẹjọ náà ni ó fi jẹ́ ìrànlọ́wọ́ sí òṣìṣẹ́ amógbá kan ní ilé ìfowópamọ́ sí AFRIbank ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
O jẹ oluṣakoso òṣìṣẹ́ nipa ofin fun ile ise Epiwit ọmọtí limited ni ìlú Ìbàdàn lati oṣu kẹfa ọdún 1991 sí oṣù tí o gbẹ̀yìn ọdún náà...
wikipedia
yo
Ní Oṣù kọkànlá ọdún 1993, ó jẹ́ ìgúnnà ilé iṣẹ́ Durtie Holdings Limited ní ìlú Ìbàdàn ti ti di Oṣù Kesán ọdún 1996, lẹ́yìn èyí ni oníṣẹ́ òfin (Legal Officer) láti ọdún 1997 sí Oṣù karùn-ún ọdún 2003..
wikipedia
yo
Folashade n ṣiṣẹ gegebi alakoso agba (abojuto) fun ile Igbimọ Idajo ti Ipinle Oyo lati odun 2003, ojo kinni osu kejo ti ti o fi di adajo agba (Chief Magistrate Grade II).Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Mustapha el-biya ni a bini ojo kejila, osu February ni odun 1960 ni taza je elere bọọlu afẹsẹgba Defender ti orile ede Morocco to ti fi wéwe..
wikipedia
yo
El Riz ṣere fun club kac Marrakech ninu Botola.aṣeyọribiyaz kopa ninu Olympic Summer ti ọdun 1984 ati Cup FIFA Agbaye ti ọdun 1986.Ni ọdun 2006, CAF yan Mustapha gẹgẹbi ọkan lara awọn igba elere bọọlu afẹsẹgba to dara ju ni ile afiRica lati igbẹjade ọdun sẹyin.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
AbDelaZ el Idrissi Boudbala ni a bini ojo kerin din lọ́gbọ̀n, osu December ni odun 1960 je elere boolu afẹsẹgba nigba kan ri..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2006, elere naa jẹ ọkan lara awọn igba elere bọọlu afẹsẹgba to dara ju ni ile afitun ti CAF yan fun igbẹdọta ọdun sẹyìn.Iṣẹ elere naa ati aṣeyọriAziz bẹrẹ iṣẹ rẹ gẹgẹbi akọrẹ Mose elere bọọlu afẹsẹgba ni WyDad Casablanca kòtòdi o lọ si FC Si, Rcing ati French Olympique Lyon..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1986, Bouderbala gba ami eye gegebi elere boolu afẹsẹgba ti odun naa.Ni odun 1986, arakunrin naa ṣere ni Cup finals agabayé ti FIFA.Ni odun 1988, Aziz je elere boolu afẹsẹgba to dara ju ninu Cup Nations ti ile afiRica.Ni odun 2015, Aziz je asoju fun Satuc Cup, eleyi lo je idije tutun lori boolu afẹsẹgba fun awon omo òrukàn U16, ọmọ Alaina ati atọrọjẹ.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Felicity Okpete Ovai (ti a bi ni 1961) je onimo ero(Brasil) ati omowe lati E°ma ti Ipinle Rivers, Naijiria..
wikipedia
yo
O jẹ ọmọ ẹgbẹ Rivers State People's Democratic Party, oun ni obinrin akọkọ ti a yan sipo Komisona fun Iṣẹ, o dipo naa mu laarin odun 2003 si 2006.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1986, Noureddine kópa nínú Cup àgbáyé ti FIFA.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Faarábìnrin kópa nínú ìdíje àwọn ọkùnrin omi ara tó fúyẹ́(men's lightweight) ni Summer Olympic tó wáyé ní ọdún 1984àwọn ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Arákùnrin náà wà lára àwọn elere tó kópa nínú Cup FIFA Àgbáyé tó wáyé ti ọdún 1986 àti 1994..
wikipedia
yo
Mustapha dije ninu Olympic ti Summer nibi to ti ṣoju fun orile ede Morocco ni ọdun 1984ji..
wikipedia
yo
Comfort Ekwu (tí a bí ní Ọjọ́ kejìlá Oṣù kọkànlá Ọdún 1954) jẹ́ ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó ti fi igbaìgbàkan jẹ́ adarí Yunifásítì ìlú Uyo.Ìtàn ayé kòpò bí Comfort Olutope Ẹgún ní Uyo ní ọdún 1954..
wikipedia
yo
Awon obi re ni Etim Udoh isok ati ńyọng sam Akpan..
wikipedia
yo
Comfort ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ Sunday School Teacher àti gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó n ran olùkó lọ́wọ́ ní Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Cross River láàrín ọdún 1983 sí 1991.Ẹk ti fi igbakan jẹ́ adarí Yunifásitì ìlú Uyo , òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti di ipò adarí Yunifásitì náà mú..
wikipedia
yo
Ní oṣù Kejìlá ọdún 2015, wọ́n yan Ọ̀jọ̀gbọ́n EnefiOk Esṣien láti rọ́pò rẹ̀ ṣùgbọ́n ó kọ̀wé sí Mínísítà ètò ẹ̀kọ́, Adamu Ádámù láti mú ìfàsẹ́yìn bá àbá láti yàn sípò náà..
wikipedia
yo
O kọwe yii latari esun ibani se ìranù esinsun yi yi iwe tiẹ̀awon oniroyin fi sun essienthe Press.Awon itọkasi..
wikipedia
yo
Zaynab Alkali (tí a bí ní ọdún 1950) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n sínú ìdílé túra-ìrẹ́ ní ìpínlẹ̀ Borno..
wikipedia
yo
O lo ile-iwe Queen Elizabeth Secondary School ti Ilu Ilorin ki o to tẹsiwaju ni Yunifasiti Àmọ́dù Bello (Abu), Zaria ati ni Yunifasiti Bayero ti Kano (Ṣóki) lati gba ami-eye Dokita(PhD) ninu imọ ingLisi.ipilẹ ati Eko rea bi Alhúkálì ni Du-ottaila ni Ipinle Borno ni ọdun 1950..
wikipedia
yo
Ó kàwé gboyè ní Yunifásítì Bayéro ti Ìpínlẹ̀ Kano pẹ̀lú àmì-ẹ̀yẹ bá ní ọdún 1973..
wikipedia
yo
ó gba àmì-ẹ̀yẹ dókítà nínu ìmọ̀ nípa ilẹ̀ Áfríkà ní Yunifásítì kan náà kí ó tó padà di adarí ilé-ìwé Shekara Girls' boarding School..
wikipedia
yo
O pada di olukọni ninu imọ ede ingLisi ni awọn Yunifasiti meji ni Naijiria.Awon itọkasiawọn Olùkọ̀wé ará Naijiria..
wikipedia
yo
jarad Anthony Honagins (ti wọ́n bí ní ​ 1998, tí ó sì kú ní December 8, 2019, tí oruko ina inagijẹ rẹ̀ n je Milionu Wld, ti kiko sile re je "Malaika World ", je àtìpó olorin ilẹ̀ ilu America, ati akọrin sile..
wikipedia
yo
O jẹ asiwaju fun àwọn ọmọ ẹgbẹ "Emọ Rapta ati "SoundCloud RapSound Rapg Rap and genres, lèyìí tí ó kọ́ ọkàn àwọn ènìyàn ní àárín ọdún 2010..
wikipedia
yo
Oruko ere itage ti o je "sise olori ile aye" ti o je jade lati inu ere sinima agbelewo "Crime thriller Film juice" (1992).Àtòjọ awon orin re Awo-orin lati Studio Goodbye & Good Riddance (2018) Death race for love (2019) Legends Never die (2020) Fighting Demons (2021) The Party Never Rabe (2023) Fọ́nrán orin rẹàwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
lábíd Khali ti a bi ni ọjọ akọkọ, Oṣu Kìíní ọdun 1955 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba to jẹ Defender fun ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede Morocco.aṣeyọrilábíd ṣere fun kac Kenitra, arakunrin naa ṣere fun orilẹ-ede Morocco ni Cup FIFA Agbaye ti ọdun 1986.Awọn itọkasiàwọn agbabọọlu-elése ara Mòrókò..
wikipedia
yo
AbdelMajid Lamriss ti a bi ni ọjọ kejila oṣu keji, ọdun 1959 jẹ agbabọọlu afẹsẹgba to jẹ Defender fun ẹgbẹ agbabọọlu orilẹ-ede Morocco.Abdelni ṣere fun Far Rabat..
wikipedia
yo
elere naa ṣere fun Cup FIFA Agbaye ni ọdun 1986.Awon itọkasiawọn agbabọọlu-elése ara Mòrókò..
wikipedia
yo
Safia Abdul Rahman tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún Oṣù Karùn-ún Ọdún 1986 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá ti àwọn obìnrin ti ilẹ̀ Ghana kan tí ó ń mú iwájú fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède Ghana..
wikipedia
yo