cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Lati akoko 1988-1992, awọn ile-iwe giga ni a fun ni ipilẹ pataki ati idojukọ lori iṣẹ apinfunni wọn bi awọn iyara ni awọn ile-ẹkọ giga ati awọn ipa-ẹkọ.. | wikipedia | yo |
Oludasilẹ ipilẹ fun Igbonla, Ọgbẹni James Akinola pàṣedà, di ilọpo meji gẹgẹbi alakoso alakoso fun awọn ile-ẹkọ giga Model marun ni ibẹrẹ ni Kínní 1988.. | wikipedia | yo |
Olori ile iwe Kankon ni Ogbeni BO Owoade nigba ti Igbakeji oga agba ni Iyaafin.. | wikipedia | yo |
Mo Omomoni.2003 lorukọMíì lati ọdun 2003, ile-iwe naa ti yipada si Lagos State Senior Model College, Kankon.. | wikipedia | yo |
Apa kekere ti ile-iwe ko si labẹ iṣakoso ti ile-iwe naa.Awọn alakoso iṣaaju Ọgbẹni Bo Owoade, 1988 to 2005 Oloye Mrs.. | wikipedia | yo |
Sowole Olley, 2005 si 2011 Ogbeni J Ashaka, 2011 si 2013 Ogbeni so FAPP, 2013 titi di oniawon itọkasi.. | wikipedia | yo |
Victoria Nwanyiocha Aguyi-Ironsi (21 Oṣu kọkanla ọdun 1923-23 Oṣu Kẹjọ ọdun 2021) ni Iyaafin Akọkọ ti Nigeria keji lati ojo 16 Oṣu Kini ọdun 1966 si 29 Oṣu Keje 1966.. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ ọ̀pọ̀ ti General Johnson Aguiyi-Ironsi ti o jẹ olori ologun akọkọ ti orilẹ-ede Naijiria.ìgbésíayé arabinrin naa wa lati Ohokobo Afara ni ijọba ibilẹ Umuahia North .. | wikipedia | yo |
ó ṣe ìgbéyàwó Johnson Aguiyi-Ironsi gẹ́gẹ́bí ọmọ ilé-ìwé ti Holy Rosary Convent School, Okigwe ni ọdún 1953 ni ìgbà ti ó wà ni ọmọ ọdún 16.. | wikipedia | yo |
ó ní àwọn ọmọ mẹ́jọ tí wọ́n mú lọ tí wọ́n sì tọ́jú wọn nípasẹ̀ àwọn arábìnrin ní Ìbàdàn lábẹ́ ìtọ́sọ́nà ti Adékúnlé Fájuyi lakoko ogun abẹ́lé Nàìjíríà .. | wikipedia | yo |
O ṣiṣẹ bi Komisona ti Igbimọ Awọn iṣẹ Ijọba Agbegbe ni Uahia .. | wikipedia | yo |
Aguiyi-Ironsi ku ni ọjọ 23 Oṣu Kẹjọ ọdun 2021 ni Federal Medical Center Umuahia lẹhin ti o jiya ikọlu .. | wikipedia | yo |
ó jẹ́ ẹni ọdún 97.Àwọn ọjọ́aláìsí ní 2021àwọn Ọjọ́ìbí ní 1923.. | wikipedia | yo |
Ìlara-mokin jẹ́ ìlú ẹ̀yà Èkìtì tó wà nínú agbègbè-ìjọba ni ìpínlẹ̀ Òndó.. | wikipedia | yo |
Ìlara-mokin súnmọ́ àwọn ilú bi Àkúrẹ́, Ìgbéragagun, Ìkóta, ẹ̀rọ, ìgbárá-òkè, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.. | wikipedia | yo |
Chike Frankie Edozien jẹ́ òǹkọ̀wé àti oníṣẹ́ ìròyìn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Òun ni adarí àgbà fún New York University, Accra, òun náà sì tún ní olùdarí fúnNew York University of Journalism.. | wikipedia | yo |
Oriṣiriṣi àpilẹ̀kọ ni ó ma ń ké tí ó sì ń gbé jáde nínú àwọn ìwé-rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Oun ni o ko iwe lives of great men, ni ọdun 2007, o si gba ebun ami-eye Lamb Literary Award fun iṣẹ rẹ naa.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yan ìwé rẹ̀ ‘Lives’ fún àmì-ẹ̀yẹ Randy Shilts Award àwọn ìwé ÀPILẸ̀KỌ ní ọdún 2018, tí ilé-iṣẹ́ ìtẹ̀wé Triangle gbé jáde.. | wikipedia | yo |
Edozien ti fi ìwé rẹ̀ yí sọ̀rọ̀ lórí òmìnira, ìfaradà àti akitiyan tí ó ṣe àfihàn rẹ̀ nínú ìwé rẹ̀ ní oríṣirṣi ìpẹ̀jọ́ àgbáyé pàá pàá jùlọ ní orílẹ̀-èdè India.. | wikipedia | yo |
Wọ́n yan Edozien’s "shea Prince" fún àmì-ẹ̀yẹ 2018 Gerald Kraak Human Rights Award àti "Last Night in Notting: ni wọ́n sa yan fún àmì-ẹ̀yẹ Gerald Kraak ní ọdún 2019, lára àwọn ìwé rẹ̀ tí ó tún gbayi ní ‘As You Like It', tí ó mú gba àmì-ẹ̀yẹ Lamb Award ní ọdún 2019.. | wikipedia | yo |
Siseyah Brown tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹfà Oṣù Kínní ọdún 1995 jẹ́ asare orí ọdán ayára pa sprinter ọmọ orile-ede Amerika.. | wikipedia | yo |
Ó kópa nínú ìdíje Women's 4 x 100 metres relay at the 2017 World Championships in Athletics.Àwọn ìtọka Siìtàkùn ìjádàwọn Ọjọ́ìbí ni 1995Àwọn Ènìyàn AlààyèAmerican Female Sekeatters Nollywood Inys Aoduates for the United StatesWorld MeOṣù MeDalists of Birth Missing (Living People)World Athletics Championships Winners.. | wikipedia | yo |
Richard àkúson (tí a bí ní Ọjọ́ Kẹrìnrín Oṣù Keje Ọdún 1993) jẹ́ Agbẹjọro ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ajá fún ètò lórí LGBTQ, Òǹkọ̀wé, olóòtú àti olùdásílẹ̀ ìwé ìròyìn tí wọ́n ń pè A Nasty Boy, èyí tíí ṣe Ìwé Àtẹ̀jáde Àkókó lórí LGBTQ+ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2019, Richard wà lára Forbes Áfíríkà ọgbọ́n tí wọ́n dárúkọ lábẹ́ ọgbọ́n Àwọn ènìyàn tí wọ́n dúró gẹ́gẹ́ bíi olùtako fún àyípadà láti tako àwọn ìmọ̀ràn lílé nípa akọ, abo, àti ìbálòpọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà níbití ìbálòpọ̀ láàrín akọ pẹ̀lú akọ àti abo pẹ̀lú abo ti jẹ́ ẹ̀sẹ̀ pẹ̀lú ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlá.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, wọ́n yàán fún àmì-ẹ̀yẹ ti The Future Award Africa's, èyí tíì ṣe àmì-ẹ̀yẹ tuntun ti Media.. | wikipedia | yo |
Richard tún jẹ́ ẹnití wón ti yàn ní èèmejì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ gégé bíi ẹni tí ó dára jùlọ nípa ìwé kíkọ lórí fashion fún àmì-ẹ̀yẹ Abryanz Style and Fashion Award.. | wikipedia | yo |
Lẹhin ifilọlẹ iwe irohin kan ti wọn n pe ni Nasty boya ni ọdun 2017, Richard wà lara àwọn ogoji ọmọ ilẹ̀ Naijiria ti o lagbara julọ ti o si wipe ojo ori i wọn ko i ti to ogoji ọdun ti YNaija dárúkọ.ibẹrẹ igbesi aye rẹ ati ẹkọ.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí Richard ní Akwanga, ní Ìpínlẹ̀ Nasarawa, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Richard ni wọ́n bí ṣe ìkejì nínú àwọn ọmọkùnrin mẹ́ta, ó dàgbà sí ìdílé tí wọn kò là tí wọn kò dára ṣagbe.. | wikipedia | yo |
Bàbá rẹ jẹ olóṣèlú nígbàtí ìyá rẹ jẹ olùkọ́ ní kọ́lẹ́ẹ̀jì.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ìwé gíga tí Shepherd's International, èyí tí ó jẹ́ lára ilé-ìwé aládàáni ti àwọn onígbàgbọ́ níbití wọ́n ti ń pèsè ibùgbé fún àwọn ọmọ ilé-ìwé.. | wikipedia | yo |
Lẹ́hìn èyí ni ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ti Ìpínlẹ̀ Nasarawa tí ó wà ní Kefi, fún ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀ àkọ́kọ́ nínú òfin.. | wikipedia | yo |
Wọ́n pèé sí ilé ìgbìmọ̀ òfin ti ilẹ̀ Nàìjíríà gégé bíi onídàájọ́ àti agbẹjọ́rò ti ilé aṣòfin àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 2017, lẹ́hìn tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ gba oyè ní ilé-ẹ̀kọ́ amòfin ti ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó wà ní Èkó.Iṣẹ́ àkúson bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gégé bíi olùkọ́ ní ará nígbàtí ó pé ọmọ ọdún méjìdínlógún.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014, ó lọ́wọ́ pẹ̀lú ṣe àgbékalẹ̀ ILLUDETE, èyí tíì ṣe pẹpẹ pínpín fọto lórí ẹ̀rọ ayélujára.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, wọ́n yàn án sí ipò láti ṣe olórí i éékà fashion àti style ti BellaNaija.. | wikipedia | yo |
Iṣẹ́ ẹ rẹ̀ ni BellaNaija mú kí ó gba àmì ẹ̀yẹ ti Abryanz style fashion.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì tún yàn án láti jẹ́ onkọwe fashion tí ó peregedé jùlọ ní ọdún 2016.. | wikipedia | yo |
Léhìn náà ní ọdún kanna ni Richard fi BellaNaija sílẹ̀ láti lọ ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ọmọkunrin PR.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2017, nígbàtí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó ṣe ìfilọ́lẹ̀ A Nasty Boy, èyí tó jẹ́ títarí ààlà àtẹ̀jáde LGTBQ+ èyí tí ó wípé láìpẹ́ ni ó dàgbà tí ó sì ní òkìkí káríayé.àròkọ ní Oṣù kẹrin ọdún 2019 Richard ṣe onígbàgbọ́ ìtàn-àkọlé kan fún ilé-iṣẹ́ CNN tí ó sì sọ àwọn oun tí ó fàá tí òun fi sá kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà wá sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà fún ààbò.. | wikipedia | yo |
Ni oṣù keje ọdún 2019, ó kọ àròkọ tí ó jẹnilọ́kàn fún ìwé ìròyìn New York Times, èyí tí ó jẹ́ ti “àtúnyẹ̀wò Ọjọ́ Sunday” tí àkọlé rẹ̀ jẹ́ “This is Quite Gay” | wikipedia | yo |
Eléyìí ni wọ́n ti jáde gbangba ní ojú abala àkọ́kọ́ ìwé ìròyìn Times ti orí ẹ̀rọ ayélujára.. | wikipedia | yo |
Bákannáà ni ó tún jáde nínú ìwé ìròhìn tí wọ́n tẹ̀ jáde lójú ewé pàtàkì tí kò farasin ní ọjọ́ Kejì.Akitiyan àti ibi ààbò Richard wá ibi ààbò lọ sí orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ní ọdún 2018 lẹ́yìn tí ó sálọ kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lẹ́yìn tí ó ti yọ nínú ìkọlù àwọn oníwà ìbàjẹ́ kan.. | wikipedia | yo |
Ní ìlú Amẹ́ríkà, ó ṣíwájú láti máa sọ̀rọ̀ ní gbangba nípa ìkọlù àti àṣà àìbìkítà nípa ìbálòpọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
O ti fi aaye silẹ fun ifọrọwanilẹnuwo pẹlu awọn imikáyà, very Goog light ati the Black Youth Project, nibiti o ti ṣe alaye lọpọlọpọ awọn oun ti o yi iṣẹlẹ burukú yii ka.. | wikipedia | yo |
Richard asíwájú láti máa jẹ́ onígboyà ajà-fún-ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn fún LGBTQ+ àti àwọn tí ó wà ní agbègbè ibi ààbò ní ìlú Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
àwọn ènìyàn alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1993àwọn agbẹjọ́rò ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Mandy La Candy jẹ́ ọkùnrin tí ó yí ara rẹ̀ padà sí obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè is a Canada tí ó ń fi orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe ibùgbé.Mandy ni wọ́n mọ̀ sí OkwuDili ṣáájú kí ó tó yí ara rẹ̀ padà sí obìnrin.Ní ọdún 2016, ó gbé àwòrán ara rẹ̀ ti òun àti ìyàwó Olórí Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà tẹ̀lé ìyẹn Melania Trump's, ìyẹn Donald Trump, fọ́tò yí ni wọ́n gbé jáde nínú ìwé kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Old Playboy Magazine tí ó ní àkòrí “If Melanie with such photos can become a first lady looking like this, why can't I". Àwọn ènìyàn alààyèLGBT people from Nigeria.. | wikipedia | yo |
Rizi Xavier timane ni ó jẹ́ olórin, Mínísítà,onkọ̀wé, ẹni tí ó yí ara rẹ̀ padà sí okùnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríã ayé rẹ̀wọn bi Timane ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́jọ, oríṣiríṣi ìdààmú ni ó bá pàdé ní ọwọ́ àwọn òbí àti olùṣọ́ àgùtàn ṣọ́ọ̀ṣì wọn nígbà tí wọ́n ṣàkíyèsí wípé nkan ọkùnrin àti ti obìnrin ni ó wà lára oun nìkan.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, wọ́n ṣe iṣẹ́ abẹ tí ó tó ogun fún láti lè yí padà kúrò lóbìnrin sí ọkùnrin.Ẹ̀tọ́ ẹ̀kọ́ àti ìṣe rẹ̀ó kẹ́kọ́ nípaBusiness Management ní London àti Los Angeles.. | wikipedia | yo |
ó tún ẹ̀kọ́ gboyè kejì nípa Social Work láti University of Southern California níbí tí ó ti kẹkọ nípa ẹ̀sìn, ẹ̀tọ́ àwùjọ àti akitiyan ní ilé-ẹ̀kọ́ ClareMont School of Theology.. | wikipedia | yo |
Ó ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bi òṣìṣẹ́ ìlera fún àwọn ọmọdé tí wọ́n jẹ́ transgender ní.. | wikipedia | yo |
John's well child and family Centre in Los Angeles.Àwọn ipa rẹ̀ ní ọdún 2013, ó ké ìwé kan tí ó pè ní "An UNspoken gbáàkú” tí ó jẹ́ ìwé tí ó tà jùlọ ní orí Amazon lábẹ́ ẹ̀ka LesBian and Gay.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014,ó gbé àwo orin kan tí ó pè ní "Love Is Stronger" ní ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
ó sì tún gbé owó kalẹ̀ láti fi rán àwọn ọmọdé tí wọ́n nílò iṣẹ́ abẹ tí òun náà ti ṣe rí .. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì ṣe ayẹyẹ ìgbéyàwó wọn elékarùn ún irú rẹ̀ lẹ́yìn ọdún mẹ́wá tí wọ́n ti wà papọ̀.Àwọn ìtọ́ka síàwọn ènìyàn alààyèNigerian Musis, producers, Writerspeople from Lagosreligious leaderstrans and Trancoll Menvarro Men.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajúmọ̀ fún ìwé rẹ̀ tí ó pe àkòrí rẹ̀ ní Fimí sílẹ̀ forever ní ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
Won yan iwe yi fun ami-eye Lamb Literary Award nibi Gay Fiction nibi idije 30th Lamb Literary Awards ni ọdun 2018.Awọn itọka si21st-Century Nigerian Novelists male Novelists People From Nigeria Nov Novsts Writers from NigeriaGay writersáwọn eniyan Alààyègun-Century Malé Writers of Birth Missing (Living People).. | wikipedia | yo |
Lọ́gán February tí wọ́n bí ní ọdún 1999 jẹ́ akéwì, alágbeyẹ̀wò orin, Alapìlẹ̀ko, akọrin, olórin àti ajìjàǹgbara fún àwọn LGBTQÌbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí lọ́gán February ní ìpínlẹ̀ Anambra ní ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹrin ọdún 1999, ó sì dàgbà sí ìlú Ìbàdàn.. | wikipedia | yo |
O keko nipa psychology ni ile-eko Yunifasiti iluIbadan.ise re ni onkowe in the nude, ti won gbe jade ni odun 2019 labe ile-ise ou ou Poetryida Poetry ati mannequin in nu ti won gbe jade ni abe ile ise ise ise oselu ni orile-ede in Amerika-ede Amerika.. | wikipedia | yo |
Oun ati ẹnìkan ni wọn pawọ́ pọ̀ kọ iwe ti wọn pe ni Painted Blue with Saltwater ni ọdun 2018.. | wikipedia | yo |
wọ́n sì kọ́ How to Cook a Ghost ni ọdún 2017 tí wọ́n gbé jáde lábẹ́ ilé-iṣẹ́ ìtẹ̀wé Glass Poetry Press.. | wikipedia | yo |
Lọ́gán jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ Pushcart fún Àkójọ Iṣẹ́ wọn bíi Mannequin in the Nude níbí Idij African Poetry Book Fund.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì tún yàn an fún ami-ẹ̀yẹ Brittle Paper.gẹ́gẹ́ bí túnsí fún LGBTQ ní orile-ede Naijiria, òun ni alapìlẹ̀ko fún "There is hope” lásìkò ipade 1990 Month ní ọdún 2020 fún lògigi yitanwon iwe rẹ̀ How to Cook a Ghost (2017) Painted Blue with Saltwater (2018) in the nude (2019)àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1999àwọn ènìyàn Alààyè-21st Nigerian pògts jíjẹ(bóyá Ibadan of Ibadan South Writers from Afro People From Nigerian Writers-ary Writers-ary Soyesis-ary Activište.. | wikipedia | yo |
William Rashidi jẹ́ ajìjàngbara fún àwọn ọmọ egbẹ́ LGBTQ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ń lọ́wọ́ nínú ìbálòpọ̀ láàrin akọ sí akọ àti abo sí abo.. | wikipedia | yo |
O jẹ ọmọ ẹgbẹ igbimọ ti o n dari ile ṣiṣi fun ilera ati awọn ẹtọ ọmọ eniyan.. | wikipedia | yo |
Oun tun ni oludari ti Equality Triangle Initiative, eyi ti o fìdíkalẹ̀ si Ipinle Delta, orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ó tún jẹ́ alágbàwí fún lílọ Prophylaxis Pre-ifihan, (PReP) láti lè fi dènà ìkọlù àrùn HIV.. | wikipedia | yo |
ní ọdún 2011, ó ṣe ìlòdì sí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlá fún ìgbéyàwó láàrin ọkùnrin sí ọkùnrin àti obìnrin sí obìnrin èyí tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé aṣòfin àgbà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ di òfin.Ẹ̀kọ́ William Rashidi kọ́ ẹ̀kọ́ gboyè jáde ni public policy láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì ti Queen Mary tí ó wà ní ìlú Londonu.Àwọn àtẹ̀jáde a Syńdémic of SypejòSocial Health problems is Associated with increased HIV sexual risk among Nigerian Gay, Bsexual, and other men who have sex with men (gbSMNA).Àwọn ìtọ́kasí àwọn ènìyàn aláàyè.. | wikipedia | yo |
Vincent Desmondjẹ oníṣẹ́ ìròyìn tí ó jọ mọ́ àṣà, ònkọ̀tàn, olóòtú àti olùpolongo ẹ̀tọ́ àwọn LGBTQ tí ó fi Ìpínlẹ̀ Èkó ṣe ibùgbé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Oun ni olóòtú àgbà fún ìwé-ìròyìn olóṣooṣù nípa Oge ṣíṣe kan tí wọ́n pè ní A Nasty Boy tí ọ̀gbẹ́ni Richard Akuson tí ó jẹ́ oníṣẹ́ ìròyìn àti amóó dá sílẹ̀ ní ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
Vincent ti ké onírúurú àpilẹ̀kọ fún àwọn ìwé ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde, àti ti orí ẹ̀rọ ayélujára tí wọ́n ṣe àgbéyẹ̀wò àti àkọsílẹ̀ nípa ẹ̀yà ara ìbálòpọ̀ ọmọnìyàn, àṣà tó gbajúmọ̀, ìgẹ̀, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.Ìgbé ayé rẹni ọdún 2020, ó fi ìmọ̀sílara rẹ̀ hàn lórí ọmọ bíbí àti jíjẹ́ obì lórí ìkànì Micro Bloeètò Svsi; níbi tí ó ti sọ wìp "Gẹ́gẹ́ bí ìrọ̀rí tẹ̀mí, kí á má bímọ jẹ́ ìwà ìmọ̀ tara ẹni nìkan. | wikipedia | yo |
Ìdí ni wípé òbí ń bí odidi ọmọ ènìyàn míràn wá sáyé lati wá ma kópa nínú làásìgbò ayé.. | wikipedia | yo |
Nioti ki ni? Se nitori ki o le wa ma ja si eto? Se nitori wipe o to ni tabi o to?”Awon ami-eye rẹàwọn ajo jẹun Nigeria fun ni ami-eye Young trailBlazer of the Year ni odun 2020 .Won yan an mo awon ti won fe.fun ni ami-eye "The 150 most Interesting Nigerians in Culture in 2019" lati owo Red Media Africa.Awon itọka si.. | wikipedia | yo |
Ezra Olubi tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kọkànlá ọdún 1986 jẹ́ olùdásílẹ̀ òwò ara ẹni, onímọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ (software developer) olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ paystack, àti ajàfẹ́tọ́ (born 12 November 1986 ).Ẹ̀tọ́ Ẹ̀kọ́ àti ìṣe rẹ̀ Ezra kàwé jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ Babcock University nínú ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ kọ̀mpútà ní ọdún 2006, òun àti Shola Akínlàdé ni wọ́n jọ pawọ́ pọ̀ dá ilé-iṣẹ́ e-payment ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sí pay sílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ezra yí tún jẹ́ jàjà, ọkùnrin tíree tún ma ń kun ètè bákan náà ní ó ma ń kun eekana pẹ̀lú.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Ṣọlá Akínlàdé jẹ́ onímọ̀ nípa software àti ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ paystack.Ẹ̀tọ́ ẹ̀kọ́ àti ìṣe rẹ̀ Ṣọlá lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama St.. | wikipedia | yo |
O tun lọ si ile-eko Babcock University nibi ti o ti lo nipa imo ẹrọ Kọmputa ti o si jade nibẹ ni ọdun 2006.O bẹrẹ iṣẹ rẹ ni Ile-iṣẹ Heineken nibi ti o ti sise gege bi alabojuto database ile-iṣẹ naa, ṣaaju ki o to lo sise pelu awon orisirisi ile ifowo-pamo ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2016, Sola àti Ezra dá ilé-iṣẹ́ paystack sílẹ̀.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Tíwálá Olanubi jnr tí wọ́n bí ní ọjọ́ dárídẹ́ osù kẹfà ọdún 1988 jẹ́ olókòwò ara ẹni lórí oúnjẹ, oníṣẹ́ ìmọ̀ èrò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Òun ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Dotts Media House èyí tí ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ilé-iṣẹ́ tí ó lààmì-laaka ní ilẹ̀ adúláwọ̀ nípa digital marketing, òun náà tún ni olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ '' zarafe loaves’’ tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ búrẹ́dì tí ó wà ní ìlú Èkó, òun náà tún ní olùdásílẹ̀ ilé-iṣẹ́ Trenduf Africa.. | wikipedia | yo |
Òun náà tún ni Olóòtú àgbà ìwé ‘’Nigerian Lìíè Marketing Report’’ (nimrr).Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
[Ìtọ́kasí nilo] titaja ńfọ̀rọ̀ pẹlu awọn ọna titaja Íńtánẹ́ẹ̀tì miiran si iwọn kan nitori awọn alajọṣepọ nigbagbogbo lọ awọn ọna ipolowo deede.. | wikipedia | yo |
Awọn ọna wọ̀nyẹn pẹlu Isapeye ero iṣhan organic (Sese), tita ẹrọ wiwa ti o sanwo (pp-Pay per Clíck), titaja imeeli, titaja akoonu, ati (ni ọna kan) ipolowo ifihan.. | wikipedia | yo |
Ni ida keji, awọn alajọṣepọ nígbàkan lọ awọn imọ -ẹrọ Orthodox ti o kere si, gẹgẹ bi awọn atunyẹwo atẹjade ti awọn ọja tabi awọn iṣẹ ti alabaṣiṣẹpọ funni.. | wikipedia | yo |
[Ìtọ́kasí nilo] titaja ńfọ̀rọ̀ jẹ rudurudu pupo pẹlu titaja itọkasi, bi awọn ọna tita mejeeji lo awọn ẹgbẹ kẹta lati wakọ̀ awọn tita si alágbàtà.. | wikipedia | yo |
Awọn ọna titaja meji naa jẹ iyatọ, sibẹsibẹ, ni bii wọn ṣe wakọ̀ awọn titaja, nibiti titaja ńfọ̀rọ̀ dalẹ́ lori awọn iwuri owo, lakoko ti tita itọkasi tọka diẹ sii lori igbẹkẹle ati awọn ibatan ti ara ẹni.. | wikipedia | yo |
[Ìtọ́kasí nilo]titaja fani nigbagbogbo jẹ aṣemáṣe nipasẹ awọn olùpolówó .. | wikipedia | yo |
[6] Lakoko ti awọn ẹrọ iṣhan, imeeli, ati idamọra oju opo wẹẹbu gba pupọ ti akiyesi ti awọn alatuta ori ayelujara, titaja ńfọ̀rọ̀ gbe profaili kekere pupọ.. | wikipedia | yo |
si, àwọn alajọṣepọ tẹ̀síwájú lati ṣe ipa pataki ninu àwọn ìlànà titaja ẹ-alatuta.. | wikipedia | yo |
[Ìtọ́kasí nilo] Iye tí a ṣafikun ti titaja Ṣótun ni otitọ pe awọn olùpolówó le ṣe ifowosowopo pẹlu awọn ọgọọgọrun awọn alabaṣiṣẹpọ, awọn Ṣókun, laisi Ikopa ni ibaraẹnisọrọ taara pẹlu wọn.. | wikipedia | yo |
Nítorínáà, àwọn olùpolówó lè pọ̀ sí ipò ọjà wọn láìsí ìwúlò láti ṣe àwọn ìlànà àtì-n gba ti àwọn ìfọwọ́sí lóòrèkóòrè àti ilẹ̀ ìbátan pẹ̀lú àwọn alábáṣiṣẹ́pọ̀.. | wikipedia | yo |
Awọn iṣẹ -ṣiṣe wọnyi ni a ṣe nipasẹ oniṣẹ Eto Ṣóté, ti o ṣe agbekalẹ olùbásoro pẹlu awọn olùpolówó ati pẹlu awọn alabaṣiṣẹpọ ati mu ki awọn olùpolówó ni anfani lati agbara ipolowo awọn alabaṣepọ lati gbogbo agbala aye.. | wikipedia | yo |
Láti ìrísí àwọn olùpolówó, àwọn iṣẹ́ ìpolówó ti pèsè nípasẹ̀ oníṣẹ́ àti kìí ṣe nípasẹ̀ alabaṣepọ kọ̀ọ̀kan tí ń ṣiṣẹ́ láàrin ètò àjọṣepọ̀.. | wikipedia | yo |
Ni afọwọṣe, awọn ṣọ̀fọ̀ (awọn alabaṣiṣẹpọ) ni anfani lati pese awọn iṣẹ ipolowo laisi ìbáraẹniṣepọ̀ eyikeyi pẹlu awọn olùpolówó niwọn Igbimọ tuntun fun awọn alabaṣiṣẹpọ ni iraye si gbogbo alaye pataki ti o nilo lati ṣiṣẹ ipolongo ipolowo kan.. | wikipedia | yo |
Irú àlàyé bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú, fún àpẹẹrẹ, àwọn ohun èlò ìpolówó fún ọjà tí a polówó àti Ẹ̀ka Iṣẹ́ Kọ̀ọ̀kan, dátà agbègbè fún àwọn ìpolówó ìpolówó olukuluku fún Ọjà tí a polówó àti Ẹ̀ka Iṣẹ́, èyítí ó lè ṣe ìkéde ní Ìbámu pẹ̀lú agbègbè agbègbè rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ni afikun, ẹgbẹ ṣọ̀fọ̀ pẹlu alaye nipa awọn oṣuwọn fun asiwaju ti ipilẹṣẹ ninu ipolongo kan fun agbegbe agbegbe.. | wikipedia | yo |
Lati irisi awọn alabaṣiṣẹpọ, awọn iṣe wọn ni a fun si oniṣẹ ati kii ṣe awọn olupolowoitan ipilẹṣẹọrọ ti pinpin owo -wiwọle igbimọ wiwajì fun iṣowo ti a tọka si - ṣaja titaja gbogbogbo ati Íńtánẹ́ẹ̀tì.. | wikipedia | yo |
Itumọ ti awọn ipilẹ ipin owo-wiwọle si iṣowo e-Commerce akọkọ waye ni Oṣu kọkanla 1994, [7] fẹrẹ to ọdun mẹrin lẹhin ipilẹṣẹ oju opo wẹẹbu agbaye.èròǹgbà ti titaja ńfọ̀rọ̀ lori Íńtánẹ́ẹ̀tì ti loyun, ti a fi sinu adase ati ìtòsí nipasẹ William J.. | wikipedia | yo |
ti ṣe ifilọlẹ lori nẹtiwọọki Prodigy ni ọdun 1989, awọn ododo CDP & awọn ẹbun wa lori iṣẹ naa titi di ọdun 1996.. | wikipedia | yo |