cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Bá kan náà ni ó kópa níbi àpérò Okòwò Àgbáyé ní ọdún 2017 tí ó sì sọ̀rọ̀ nípa ètò àwọn LGBT ní inú àpérò náà níbi tí ó ti sọ̀rọ̀ nípa pàtàkì àwọn LGBT ní ibi iṣẹ́.Ó ti kọ ìtàn tí wọ́n ti sọ di eré tí ó sì tún jẹ́ adarí eré náà tí wọ́n pè ní under tẹ Rainbow, eré tí ó dá lé bí obìnrin ṣe ń sọ̀kò obìnrin, irúfẹ́ àkọ́kọ́ irú rẹ̀ tí wọ́n yóò gbé jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
ní ọdún 2019, wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ Mary Chinwa Award ti orúkọ nrẹ̀ sì jáde níbíe ní ọdún 2018.Ife Pamela fi èrò rẹ̀ han nípa gbígbé ère kan jáde tí yóò dá lé bí obìnrin ṣe ń sọ̀kò obìnrin tí ó lè ní ìfẹ́.. | wikipedia | yo |
Orísirísi àríwísí ni ó wáyé lórí èrè tí ó ní òun fẹ́ gbé jáde náà látàrí bí ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lábẹ́ ìṣèjọba Goodluck Jonathan ti fòfin de ẹ̀tọ́ LGBT.. | wikipedia | yo |
Oun ati gbaju-gbaja osere Uínlé Ikpe-Etim pẹlu Àjọ Ẹquality hub ni won jo pana gbe eré naa jade.. | wikipedia | yo |
Eré yí ni ó jẹ́ eré àkọ́kọ́ tí yoo dá le bí obìnrin ṣe n kòwá obìnrin tàbí LGBT ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Eré náà rí nító orírírí látàrí àyẹ̀wò tó dádò ìwé tí ó tí ó ṣe àyẹ̀wò eré sí ní má àgbéléwò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Kódà àjọ náà fi àtìmọ́lé dùn kokoko mọ́ àwọn òṣèré náà bí wọ́n bá gbé eré náà jáde.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn ènìyàn alààyèNigerian Activištets Women Writers Writers documentary filmrs Film Finnt ScreenWriters-21st Nigerian WomenLGBT People From Nidele of Birth Missing (Living People)University of Baltimore alumni University of Wisconsin-Superior Alurírán University alumnipeople from Cross River StatePeople From Calabar.. | wikipedia | yo |
James Obialor ti gbogbo eniyan mo si James Brown ni won bi ni ojo kejilelogun osu keji odun 1999 je onise ori ero ayelujara, onijo ati Cross DRana ti o di gbaju-gbaja ni ọdun 2018 latari fọ́nrán kan ti o di toro fọ́nkálẹ̀ lori ero ayelujara ti won so wipe "They did not caught Me" leyin ti awon olopa mu.. | wikipedia | yo |
Awon ni won mubpelu awon eniyan mẹ́rìndìnláàdọ́ta kan ti won fura wipe won je LGBT, ti won si lo nkan bi osu kan ni ogba atunṣe ti o wa ni Ikoyi.. | wikipedia | yo |
Loyìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ akitiyan, ile-ẹjọ da wọn silẹ.James Brown gbe awọnorin kan jade ti o pe ni “He Dulings” ni ọdun 2021.ija oun ati Bobrisky ni inu osu kini ọdun 2021, awọn alabojuto Instagram ti oju-ewe James Brown pa leyin ti o ṣe fanran kan ti o fi sọ wipe Bobrisky fi esun kan oun wipe oun n se bi Bobrisky pẹlu ìṣesí ati ara mimu oun, ati wipe Bobrisky Dte iku si oun.. | wikipedia | yo |
Bobrisky fi ẹyin owó da ọ̀rọ̀ rẹ nù, ó James sì ṣe fọ́nran miran lati bá Bob lori YouTube.Awon itọka si awon eniyan Alààyè Entertainment Industry GisePeopleLGBTLGBT People From Nigeria-DRvcare Gender and Tranìdáni People Ọjọ́ìbí ni 1999.. | wikipedia | yo |
Bobrisky jẹ eniyan pataki lori Íńtánẹ́ẹ̀tì ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
O jẹ obinrin ti a tun mọ si trans woman ni ile Naijiria, orile-ede ti ko ni awon eto fun LGBT.. | wikipedia | yo |
O tun jẹ eni ti o ma n sábàá fi arahàn lori ero ayelujara ti awujo media ti won n pe ni snapchat.ibẹrẹ igbesi aye ati ẹkọ Bobrisky okuneye Idris Olarenwaju ni eni ti o bi Bobrisky ni odun 1992.. | wikipedia | yo |
Ó parí ilé-ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírì ní King's College, tí ó wà ní Èkó kí ó tó wá tẹ̀ síwájú lọ sí ilé ìwé gíga Yunifásítì ti ìlú Èkó Yunifásítì ìlú Èkó (UNI).. | wikipedia | yo |
ní oṣù karùn ún ọdún 2019, Bobrisky jẹ́ ẹ̀rí si wípé àwọn ọ̀rọ̀ oyè ẹ rẹ jẹ́ “oun” àti “rẹ” lẹhin gbígba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àsọyé àṣìṣe lórí i profaili rẹ Instagram rẹ.Ẹ̀yà an rẹ Bobrisky jẹ́ ẹni ti àwọn ènìyàn mọ daada lórí ẹ̀rọ ayélujára ti àwùjọ media láti àwọn àríyànjiyàn tí ó ma nṣe lórí àìfaramọ́ àwọn òdìnwọ̀n ìhùwàsí àtijọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Bobrisky ni anfani lati ko awon iroyin jo lori snapchat rẹ, nigbati o sọ pe oun ni ololufẹ kan ti oun ma n ro wipe o je akọ laibikita ofin ile Naijiria ti o so wipe awon ìbáṣepọ̀ ni aarin awon ibalopọ kan naa je ese ti o je ijiya nipa sise ewon odun merinla.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kẹjọ oṣù keje ọdún 2021, ó ṣàfihàn ara rẹ̀ tuntun lẹ́hìn tí ó ti lọ ṣe iṣẹ́ abẹ láti túnbọ̀ di àbọ̀ síi.Ìfarahàn Bobrisky, nípa agbára tí ó wà tẹ́lẹ̀, ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ìlànà iṣẹ́ àti ìwà sí àwùjọ ni Nàìjíríà èyí tí kò wà ní ìbámu pẹ̀lú ìhùwàsí àwùjọ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Biotileje wipe awon die kan wa ti won fi Arakọja iwa ati ìṣesí rẹ, bakanna an ni awon kan an wa ti won ta ko o.. | wikipedia | yo |
Nibi ayeye pataki kan, enikan ti o je amugbalegbe aare orile-ede Naijiria fi agbegbe kan sile nitoriti o se akiyesi wipe Bobrisky wa ni aarin ibugbe naa.Bobrisky ni ìwọnba àwọn alátìlẹyìn ti wọn ni ifẹ rẹ ti o fi jẹ wipe awon oluṣe eto ayeye kan ma a npe e lati wa sọ awon oro nibi ise ayẹyẹ wọn ti wọn gba.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 2019, ọ̀túnba Olusegun Runwe eniti i se oludari gbogboogbo ti Igbimọ orile-ede Naijiria fun Iṣẹ ọna ati asa, sọ ninu oro re wipe Bobrisky je "itiju orile-ede” ati wipe ijiya ti o nipọn ni won ma a fi je e ti won ba mu u ni opopona.Ipa Taiwo Kola-Ogunlade, eni ti i se olubanisoro ati alakoso eto nipa gbogbo eniyan lori ero ayelujara ti Google fun iwo-oorun ile Afirika, sọ wipe Bobrisky ni eni ti wọn n wa kiri julọ ni Naijiria lati ojo kerindinlogbon osu kewaa si osu Kọkànlá odun 2016.Awon itọkasi awon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1992.. | wikipedia | yo |
Teemie Ovwàsá tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànọgbọ̀n Oṣù Kọkànlá ọdún 1996 ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí YBNl Princess, ni ó jẹ́ olórin , Olùkọrin, àti òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó sì ń akọrin pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ àgbọ̀rín-jáde YBN Nation nígbà tí ó fọwọ́ sí ìwé àdéhùn pẹ̀lú wọn ní inú oṣù kẹjọ ọdún 2015 àmọ́ tí ó kúrò ní ilé-iṣẹ́ náà ní inú ọdún 2020 lẹ́yìn ti èdè òun àti Ọládé tí ó ni ilé-iṣẹ́ náà kò fẹ́ jọra mọ́.. | wikipedia | yo |
Ovbu ni o fi han fáyé wipe obinrin bi ẹgbẹ oun ni oun nifẹ si lati ma ba ṣe àṣepọ̀.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ó di ọdún 2020, ó gbé orin rẹ̀ àkọ́kọ́ irú rẹ̀ tí ó ke nípa bí okùnrin ṣe ń ní àṣepọ̀ pẹ̀lú okùnrin ẹgbẹ́ rẹ̀, èyí tí yóó mú kí ó jẹ́ irúfẹ́ rẹ̀ àkọ́kọ́ irú rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí Ovwàsá ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n iṣẹ́ kọkànlá ọdún 1996 ní ìlú Ìlọrin tí bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Delta tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Osun.. | wikipedia | yo |
Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ tí Grace Christian Schools tí ó sì lọ sílẹ̀ ẹ̀kọ́ girama tí Dalex Royal College, ní Ìlọrin.. | wikipedia | yo |
Ó kẹkọ nípa Medical Anatomy níṣe ẹkọ Ladoke Akintola University of Technology.Iṣẹ orin rẹ Temie bẹrẹ orin rẹ láti nkan bi ọmọ ọdun mẹjọ gege bi akọrin ni ile-ijọsin won nibi ti o ti kọkọ gbe orin tirẹ silẹ. | wikipedia | yo |
Látàrí ẹ̀bùn orin tí ó ní yí, ìyá rẹ̀ ra jìtá tuntun kan fún nígbà tí ó lé ọmọ ọdún méjìlá.. | wikipedia | yo |
Ó di gbajú-gbajà ní ọdún 2015 nígbà tí Ọládé pẹ́ẹ́ lórí Instagram tí ó sì gbà á wọlé sí inú ilé-iṣẹ́ àgbọ̀rín-jáde rẹ̀ yBNl níbi tí Bámómóe ti gba ìnagijẹ '' ''y Láf’’ | wikipedia | yo |
S Tevmie si fi YBNL sile leyin Àìgbọ́ra eni ye ti o sele laarin oun ati Olamide.Awon awo orin Reawo e Be Like Say dem swear for Me (2020)orin Àdàkọ re Afẹ́fẹ́ (2016) JáBO (2016) Bámidélé (2017) Holy Water Water (2018) Osun Osun (2020) Ẹlẹ́jọ́ wẹwẹ wẹwẹ (2020)Àwọn Itoka si awon eniyan Alààyè Tuntun-ama singer-ama Ọjọ́ìbí- Nine-Agege Sabe'LGBT People People Mevel Rights EleVojvodinats from Nigeria.. | wikipedia | yo |
akudo ZAghamba ni o je a ja fètò Ọmọnìyàn, Olùkọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti kọ́ ìwé iwadi nípa ẹ̀tọ́ àwọn LGBTQ.. | wikipedia | yo |
Oun ni oludasile ajo Women's Health and Uv Rights (WRA) o si tun jẹ ọkan kan soso lara awọn oludasile Pan-African Ilga (International LesTgaines, Gay, bisexual, trans and InterSex Association) ati equtyl - International Centre for Human Rights OvAghamba je akekoo jade ile-eko University of Nigeria, Nsùúwon itọka si.. | wikipedia | yo |
Seyi AdeBanjo ni o je GenderFluxid, Queer MFA Media Artist, ti o je omo orile-ede Naijiria ti o si ti fi ilu New York City se ibugbe bayi ni o ni lokan lati ma se ipo loo fun awon ipenija ti o n doju ke ẹya, adámọ ajo ati abo tabi ibalopọ nipa yiya aworan, sise Fonra, tabi ere agbelewo ati awon apileko orisirisi nipa lilo awon ikani ibani-Doré.Àwọn ise readeBanjo ti se afihan awon ise Ola-O-irin-kan rẹ ni awon ile ise nkan kerindinlogbon ojo si paa paa julo ni Museum of the City of New York, Bronx Academy of arts and Dance (baa,’d] Longwood art Gallery and Skylight Gallery-to plaza Corporation Corporation, Leslie-man Museum of Gay and Lesdúńbú Art ati oníjàgídíjàgan Waterloo arts Gallery.. | wikipedia | yo |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyĩ, àwọn iṣẹ́ rẹ̀ wà lábẹ́ Bronx Museum.. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni wọ́n tún wà pẹ̀lú Fellow The Laundrọmat Project, Queer/art/mentosọ̀rọ̀sọ̀rọ̀, Maysles Institute, Independent filmmaker Project, àti City Lore.Ìwé ìròyìn olóṣooṣù tí African Voices Magazine, Osun State University, Q-Zine, àti Dedven Duroven Herald ti gbé oríṣiríṣi iṣẹ́ tí Adébanjo ti gbé Haide.. | wikipedia | yo |
Eré tí ó jẹ́ oní ìṣẹ́jú keje ní tí ó dá lórí iṣẹ́kúpa obìnrin tí ó jẹ́ transgender tí wọ́n ń pè ní Islan kòles ni ó gbé jáde ní inú Oṣù Keje ọdún 2013.. | wikipedia | yo |
Ile-iṣẹ pbs ti wa lori ikani ketala (13) ṣe afihan ere naa, pẹlu Brooklyn Museum.. | wikipedia | yo |
Bá kan náà ni wọ́n ṣe afihan rẹ káàkiri agbaye, ti o fi mọ BFI Flare ní London, wọ́n tún ṣe afihan rẹ lori LGBT Film Festival, Gender Reel Film Festival, Al Jazeera America, àti Black Star Film Festival.Ọya! Something happened on The Way to West Africa! Ni o jẹ èrè ọ̀laọgbọ̀n iṣẹju ti o wa sakun ẹya àti ìbálòpọ̀.. | wikipedia | yo |
Eré yí ní ó ṣe ìsẹ̀jú ìrírí ẹ̀yà ọmọ Nàìjíríà tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà míràn tí ó wà ní ìlú New Yorw àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ Adébanjo ti gba àwọn àmì-ẹ̀yẹ tí ònkọ̀tàn tó peregedé jùlọ ní orí Short Award ní Ibi ayẹyẹ Drama Baltimore International Black Film Festival, Reel 13 Short Film Award, Dfish parade 2015 Grand Marshal | wikipedia | yo |
O tun gba ami-eye ti Best International Short Film ni Sydney transgender International Film Festival , ati idaraya of the Ocean LGBT Film Festival Award Award ati hunter College's Dean of Arts & Science Master's Thesis support Grant.Awọn itọka Kapa Le Birth Kapa (Living People) Eniyan AlaniLGBT People From Nigeria Artists from Nigeria.. | wikipedia | yo |
Uàbáji Ikpe-Etim tí wọ́n bí ní ọdún 1989 jẹ́ olùgbéré-jáde àti ònkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó kéde fún ètò àwọn LGBT gẹ́gẹ́ bi àwọn ènìyàn kan tí wọ́n ń fi ètò tó wò wọ́n níá ní.. | wikipedia | yo |
Ni inu ọdun 2020, ile-iṣẹ BBC fi orukọ rẹ si ara awọn eniyan Ọgbaọrun un obinrin fun ọdun 2020 (100 Women of the Year).ibẹrẹ Aye rẹ wọn bi Etim ni wọn bi ni ọdun 1989.. | wikipedia | yo |
Òun àti ẹnìkan ni wọ́n jọ dá ilé-iṣẹ́ hashtag Media House, ó sì ti ń ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn àwùjọ kéréje-kéréje pàá pàá jùlọ àwùjọ LGBTQ láti ọdún 2011.. | wikipedia | yo |
O ri wipe awon eniyan n foju pa iyaba eto awon LGBT ni ile Adulawo, paa paa julo ni orile-ede Naijiriati o fi mo awon ile ise agbere-jade gbogbo ni orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ní ilẹ̀-iṣẹ́ Nollywood, gbogbo eré tí ó bá ti jẹ mo ti LGBT ni wọ́n ma ḿ fi ṣe yẹ̀yẹ́, tàbí kí wọ́n sọ pé ẹ̀dá ìtàn náà wà ní inú ẹgbẹ́ òkùnkùn tàbí kí wọ́n sọ wípé onítọ̀hùn wà nínú ìgbèkùn tí wọn yóò sọ wípé àfi kí wọ́n gbé wọn lọ sí ilé ìjọsìn fún ìtúsílẹ̀.. | wikipedia | yo |
Eré èyí tí wọ́n bá gbé jáde tí ó jẹ́ ti LGBT ní ó sábà ma n jẹ́ ti àwọn okùnrin tí wọ́n jẹ́ Homosexual.ní ọdún 2020, Etim àti akẹgbẹ́ rẹ̀ kan Pamela Adie di lààmì-laaka ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú bi Eọ̀n ṣe gbé eré kan tí ó ní ṣe pẹ̀lú LGBT jáde tí wọ́n pè ní ìfẹ́.. | wikipedia | yo |
Ere yi ni o gbe Etim jade gẹgẹ bi adari ere, ti wọn si fi ere naa sọ nipa ọrọ ifẹ ti o ṣẹlẹ láàrí awọn obinrin meji ti wọn jẹ ololufẹ.. | wikipedia | yo |
Eré onítàn ìfẹ́ kìí ṣe eré tí yóó ma sọ nípa LGBT ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, amo òun ní ońn àfihàn ìbáse abọ́ méjì tí kò sì mú ìlù sí omi ó tó láti ọ̀dọ àwọn ará ìlú.. | wikipedia | yo |
Lóòtọ́ ni wípé gbogbo àwọn tí wọ́n kópa nínú eré náà láti olùdarí ère, olùgbéré-jade àti àwọn olú ẹ̀dá ìtàn ni wọ́n jọ jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ LGBT.. | wikipedia | yo |
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé, àjọ tí wọ́n ṣe ìgbéléwọ̀n àwọn eré sinimá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kọ̀ jálẹ̀ wípé wọn kò gbọdọ̀ gbé eré náà jáde tí wọ́n sì tún dùn kọ́kọ́ mọ́ àwọn òṣèré náà wípé wọ́n yóò lọ sẹ́wọ̀n bí eré náà bá fi jáde, látàrí wípé wọ́n ní wọ́n gbé kí ọkùnrin àti ọkùnrin ó má fẹ́ra wọn ní ohun tí òfin orílẹ̀-èdè wọn kò sì fàyè gba irúfẹ́ nkan bẹ́ẹ̀ láti ọdún 2014.. | wikipedia | yo |
Lati yàgò fun ijiya ijọba orilẹ-ede Naijiria, wọn lọ gbe ere naa jade ni Ilu London ni inu osu kẹwàá ọdun 2020 ni Toronto LGBT Film Festival.. | wikipedia | yo |
Wọ́n sì n ṣàfihàn rẹ̀ ní orí ìtàkùn ehTVNetwork.com.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún ṣe àfihàn rẹ̀ ní Leeds International Film Festival in November 2020.Àwọn Ieye siílẹ̀-iṣẹ BBC yan Ikpe-Etim mọ́ àwọn ọgọrun obìrin tí wọ́n fẹ́ fún ní àmì-ẹ̀yẹ 100 Women fún ti ọdún 2020 láti fi gbóríyìn fún lóri bi ó ṣe ń ṣe àtìlẹyìn fún ẹ̀tọ́ àwọn LGBT ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́ka síExternal Shade Cindy Ámádi And Ú-àbá Ikpe-Etim Talk About Their Film Ifẹ̀àwọn Ọjọ́ìbí ní 1989àwọn Ènìyàn Alààyè, Film Directors féminin Women Film Directors Directors féminin Directors Directors 100 Women.. | wikipedia | yo |
David William Gentleman RDI jẹ́ òsèré gẹ̀ẹ́sì tí abí ní ọjọ́ kọkànlá , Oṣù Kẹta, ọdún 1930.. | wikipedia | yo |
O kẹkọọ apejuwe ni Ile Eko Royal College of Art labẹ akoso ati John Nash.O kẹkọọ apejuwe ni Royal College of Art labẹ Edward Bawden ati John Nash .. | wikipedia | yo |
O ti sise ni awọ-omi, lithography ati kiko igi, ni awon iwon ti o wa lati awon pẹpẹ gigun pẹpẹ fun Charing Cross Underground Station ni Ilu Lọndọnu si awon ontẹ ati awon apejuwe.Awon eniyan Alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1930.. | wikipedia | yo |
Moji Solale-Wilson ti won bi ni odun 1968, ni o je omo bibi Ilu Ijero Ekiti ni Ipinle Ekiti.. | wikipedia | yo |
) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè a Nàìjíríà, àmọ́ tí ó fi ìlú Wngland ṣe ibùgbé jẹ́ alàgàta láàrin (dọdẹ) Onta àti òǹra, ó ń báni ralé ralé, bẹ́ẹ̀ ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn LGBTQia+, a ja fètò ọmọnìyàn, aláríwísí àwùjọ àti olùdásílẹ̀ Solar worlwide inu.Ní ọdún 2017, ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ọọbìnrin ẹgbẹ́ rẹ̀ Margaret Wilson, ó sì di obìnrin àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí yóò dán irú rẹ̀ wò.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1968àwọn ènìyàn AlaniLGBT People From NigeriaLGBT Eledun Fromvište from Nigeria.. | wikipedia | yo |
Cyril Ikechukwu nri ti won bi ni ojo kaaládéi osu kerin odun 1961.. | wikipedia | yo |
jẹ́ British-Nigerian òṣèré, ònkọ̀tàn àti adarí eré tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Adam Okà nínú eré Àtìgbà-dègbà orí amóhù-máwòrán The Bill.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀baba àti ìyá nri jẹ́ ọmọ ẹ̀yà Igbo tí wọ́n sá ládé fún ẹ̀mí wọn ní àsìkò ogun abẹ́lé Biafra bẹ́ sílẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdú 1968. | wikipedia | yo |
Oun ati awon obi re ko lo si orile-ede Portugal nigba ti no wa ni omo odun keje, won si tun ko lo Ṣilondon leyin naa.nri lo si ile-eko asoju Park School I mm ti o wa niapa iwo oorun ilu London, ibe ni o ti bere si n kopa ninu ere-itage bii bii laarin ebi keru.. | wikipedia | yo |
O tun lọ si Ile-ẹkọ The Young Oluvic Youth Theatre ti o wa ni agbegbe Waterloo ni London.. | wikipedia | yo |
O tun kẹkọọ ere onise ni Bristol Old Oluvic Theatre School.. | wikipedia | yo |
Agbegbe South London ni nri n gbe lati ọdun 1980s.Iṣẹ rẹ gege bi ọṣẹrenri di gbajumọ latari ipa rẹ ti o ko gege bi eda itan Adam ọkàro, ninu ere agbelewo ori amo-máwòrán ITV ti won pe akori re niThe Bill.. | wikipedia | yo |
Ó tún kópa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn Graham níbi tí ó ti jẹ́ agbẹjọ́rò òun àti Miles àti Anna, nínu eré onípele tí wọ́n ń ṣàfihàn rẹ̀ ní orí amóhùmáwòrán-máwòrán BBC TV tí wọ́n pe àkọlé rẹ̀ ní This Life.Lẹ́yìn tí Cyril kẹ́kọ ìmọ̀ eré oníṣe tán, ó bẹ̀rẹ̀ sí ń wèrè jẹun Níb Royal Shakespeare company níbi tí ó ti kọ́kọ́ kópa gẹ́gẹ́ bí Lucu nínú eré tí Ron Medáì's gbé jáde ní ọdún 1982 tí wọ́n pe àkọlé rẹ̀ ní Julius Caesar.Ó tún kópa gègé ẹ̀dá ìta ìtàn Ariel nínú eré The Tewúra.Ní ọdún 2008, ó tún kópa nínú eré waking the Dead tí wọ́n ń ṣàfihàn rẹ̀ ní orí ẹ̀rọ amóhùmáwòrán-máwòrán BBC.Ó sì tún kópa nínú eré The Observer ní Royal National Theatre.Ní ọdún 2009 àti 2010, ó kópa nínú eré Law & Order UK tí ó sì tún kópa nínú eré yí kan náà tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2012 àti ọdún 2013.Ní inú oṣù kọkànlá ọdún 2010, ó tún kópa nínú ìpele kẹrin eré The Sarah Jane Adventures, “lost in Time" | wikipedia | yo |
Ó sì padà tún kópa nínu ìbẹ̀rẹ̀ ìdi karùn-ún eré náà ní ọdún 2011, "Skyni ọdún 2016, ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti British Academy Television Award fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ẹ̀dà ìtàn lance nínú eré Russell t.. | wikipedia | yo |
Davies ti Obrujẹ́ ọ̀kan lára eré onípele orí amóhùmáwòrán-máwòrán cucumber.Ó tún kópa nínú eré Goodnight Sẹ̀artthe níbi tí ó ti kópa kópa bí dókítà ní ilé ìwòsàn ti ìyàwó Yvonne sparrow ti bí àbíkú.Ó kópa nínú eré oníṣe kan tí ó jẹ́ ti ilé iṣẹ́ Asọ̀rọ̀-mágbèsì BBC gbé kalẹ̀ ní ọdún 2020.. | wikipedia | yo |
Noughts and Crosses.Ìgbé ayé Renri ni ó ti ṣe igbeyawo ri àmọ́ ó ti di Gay bayi.. | wikipedia | yo |
O ti ni awon omo meji ti won ti dagba.Awon ere ti o ti kopa Strapless (1989) ..... | wikipedia | yo |
Barrister Julian Btes / Irúdò Dider Adam Oká / Pascal illunga Runaway Bay (1992, TV series) .. | wikipedia | yo |
Council Computer operator Pita in the Sky (1996, TV series) .. | wikipedia | yo |
Security Officer a chch of Frost (1999, TV series) .. | wikipedia | yo |
Warren Barber Family Affairs (2000, TV series) ..... | wikipedia | yo |
William MChugh Aradepo Nights (2000, TV mini-series) .. | wikipedia | yo |
Pastor Carl / Lawrence Marshall / Ben Sinclair Down to Earth (2001, TV series) ..... | wikipedia | yo |
Inspector Tony Callaghan / Thomas Hazimana / Mark Harmer / Andrew Lomba Long Time Dead (2002) .. | wikipedia | yo |
Adam Okárọ Murder Investigation team (2003, TV series) .. | wikipedia | yo |
Restaurant manager waking the dead (2008, TV series) ..... | wikipedia | yo |
Judge DeMarco Tinga Tinga Tales (2010, TV series) ..... | wikipedia | yo |
Apecock the Sarah Jane Adventures (2010-2011, TV series) .. | wikipedia | yo |
The shopKeeper House of AnuBis (2011, TV series) ..... | wikipedia | yo |
First Order Officer #2]Àwọn Itoka síàwọn àsopọ̀ Ìta Àwọn Ènìyàn AlààyèÀwọn Ọjọ́ìbí ní 196120-Century English Malé Actors Ewu-Century Malé Actor of Bristol Old National Theatre School Àjàpá Àjàpá Actors British Maete Actor Ma film Actor Maengls Soap opera opera Ẹ̀yín Maete Television Peopleeng People of Nigerian Descente People of Igbogbo RanOlùgbọ́gbo Maroko Black Black British People GLGBT From England People From Niani Ẹmiani Ibi The United Kingdom at the Atcated Park Park School.. | wikipedia | yo |
Ayodele Olofintuade jẹ́ òǹkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, oníròyìn àti ẹ̀yà abo.. | wikipedia | yo |
O ti se afihan ara rẹ gege bii eni ti kii se alákọméjì ni orile-ede Naijiria, orile-ede ti o se ilodi si LGBTQ .Ìgbésí ayé e re a bi Ayodele Olofintuade ni iluIbadan, orile-ede Naijiria ni odun1970.. | wikipedia | yo |
Ní àárín Èkó, Ìbàdàn àti Abeokuta ni Olofintuade dàgbà sí.. | wikipedia | yo |
Ó ń ṣe àtìlẹ́yìn fún ara rẹ̀ lórí ìwé kíkọ tí ó yàn láàyò.. | wikipedia | yo |
Ní pàtàkì ni ó jẹ́ wípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé tí ó ti kọ ni wọ́n dá lórí i Ẹ̀yà abo ní ilẹ̀ Áfíríkà, àwọn ohun ti èmi ni ilẹ̀ Yorùbá (káàkiri ilẹ̀ Áfíríkà títí tí ó fi dé ẹ̀yà adúláwọ̀ tí wọ́n jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè ìlú aláwọ̀ funfun), LGBT ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní agbègbè àti ẹ̀yà tí kò ní ìbámu ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
A dáamọ̀ gẹ́gẹ́ bí queer, àti ẹ̀yà abo tí kìí ṣe alákọméjì.Àwọn ìwé tí ó ti kọ.. | wikipedia | yo |
Iṣẹ rẹ akọkọ pataki ti o jẹ ti Litireso ni itan Eno, eyiti ile-iṣẹ itẹṣan Nanava Republic ṣe atẹjade rẹ ni ọdun 2010, iwe lori itan awon ọmọde eyi ti won yan lati gba ẹbun ti Orilẹ-ede Naijiria fun iwe Litireso ti o dara julọ ni ọdun 2011.. | wikipedia | yo |
Ìwé Lítíréṣọ̀ yí sọ̀rọ̀ lórí gbígbé àwọn ọmọdé káàkiri láti lọ máa fi wọ́n ṣe òwò ẹrú, èyí tí ó ti ń mú ìfàsẹ́yìn bá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ọjọ́ tí ó tipẹ́.. | wikipedia | yo |
iwe Atiku Pàtàkì àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ kọ́ lórí àwọn ènìyàn LGBTQ tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Ìbálòpọ̀ tí A-B-C lórí ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà èyí tí àtẹ̀jáde rẹ̀ wáyé ní ọdún 2014 lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ lẹ́hìn tí wọ́n ṣe àgbéyẹ̀wò òfin ìgbéyàwó akọ sí akọ àti abo sí Abo ti ọdún 2013 gẹ́gẹ́ bí èyà lára àwọn irinṣẹ́ tí àwọn adájọ́ yíò lò fún ìkéde òfin náà.. | wikipedia | yo |
Ìwé rẹ àkọ́kọ́ tí wọ́n tẹ̀ jáde ní ọdún 2011 ni ó wà lára àwọn ìwé tí wọ́n yà sí ọ̀tọ̀ fún ẹ̀bùn ti Nàìjíríà fún ti ìwé Lítíréṣọ̀.. | wikipedia | yo |
Orísirísi àwọn ìwé ìròyìn àti àwọn ìwé àkọsílẹ̀ nípa ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n ti ṣe àtẹ̀jáde àwọn iṣẹ́ rẹ tí ó fi mọ́ níṣìíríana Talk àti Anathema.. | wikipedia | yo |
Olofintuade tún jẹ́ Olùdarí àti alákóso fún ojú òpó tí wẹẹbu kan tí ó wà fún ipa òdì ti àìdọ́gba.. | wikipedia | yo |
Olofintuade ní ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa ìṣe, èmi àti àṣà Yorùbá, ó jẹ́ lílò pàtàkì fún àwọn ọ̀dọ́ òṣèré.. | wikipedia | yo |
Lagos State Senior Model College Kankon je oun ini ijoba ilu Eko to je ile eko giga ni opopona Owode-Apa ni Badagry LGA, Lagos State .. | wikipedia | yo |
O ti da ni ọdun 1988 lakoko iṣakoso Ologun ti Rear Admiral Mike Akhigbe (rtd).Ìtàn LSMC Kankon jẹ ọkan ninu awọn kọlẹji awoṣe marun ti a ṣeto ni ọkọọkan ninu awọn ipin marun lẹhinna ti Ipinle Eko .. | wikipedia | yo |
Ile-iwe naa gbe lọ si aaye ti o wa titilai ni opopona Owode-Apa ni Oṣu kọkanla ọjọ 27, ọdun 1989.. | wikipedia | yo |
O ti dasilẹ ni ọdun 1988, pẹlu awọn kọlẹji awoṣe mẹrin miiran labẹ iṣakoso ologun ti Captain [[Okhai Mike Akhigbe, Gomina Ologun ti ipinlẹ Eko nigbana.. | wikipedia | yo |
Ile-ẹkọ giga ti a dasilẹ pẹlu awọn mẹrin miiran waye ni Ile-ẹkọ giga ijọba, Ketu, Epe.. | wikipedia | yo |
Awọn ile-iwe giga awoṣe mẹrin miiran pẹlu Igbonla, Badore, Meiran ati Igbokuta.. | wikipedia | yo |