cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé wọ́n ń pè fún ṣíṣe àbójútó tó lọ́ọ̀rìn sí bí ìjàmbá ṣe ń ṣẹlẹ̀ ní ojú ọ̀pọ̀ àwọn ọkọ̀ ojú-irin..
wikipedia
yo
mor tún gbé ró láti ta bón tí ó tó ẹlẹ́orun ún kan bilionu owó yuan tí ó jẹ́ ($14.6 billion) láti fi fẹ́ ojú ọ̀nà ọkọ̀ ojú irin jákè-jádò ilẹ̀ China ní ọdún 2009.Àwọn ilé-iṣẹ́ tí wọ́n ní ọkọ̀ akérò ojú irin àwọn àjọ tí wọ́n ń ṣàkóso àwọn ọkọ̀ ojú irin jẹ́ mẹ́rìndínlógún(16) nígbà tí ilé-iṣẹ́ ọlọ́kọ̀ ojú irin tí wọ́n wà ní abẹ́ ilé-iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ fún ìgbòkègbodò ọkọ ojú irin jẹ́ méjì péré..
wikipedia
yo
Iye awon ti won n sise ni abe ile-ise yi ni nkan bi odun 2098 je Milionu meji eniyan.Àkójọ awon Minisita ti won ti dari ajo naa nìwọ̀nyíe tun le wo Ministries of the People's Republic of China Ministry of Transport of the People's Republic of China National Railway Administration China Railway Corporation China Railway Museum Liu Zhijun itọka siìtàkùn ija ṣóde China Academy of Railway Sciences National Railway Administration Chinways Chinamístries established in 1949dect government departments of China..
wikipedia
yo
Eyi ni atojo oruko awon eniyan pataki ti won je omo Amerika sugbon ti orírun won je China..
wikipedia
yo
Awon oruko wonyi je ti awon ti won koja si Amerika fun ara won tabi awon omo Amerika sugbon ti iran won je ti China ti won sin ti se nǹkan pataki láwùjọ lórílẹ̀-ede Amerika.Awon onise-ọ̀nààwọn onijo GH Dulle San (wu Zhu Shan ) - onijo Ballet ati onijo ẹsẹẹsẹ Shen We We (chen We ) - dancer, onijo ẹsẹẹsẹ ati ayaworan; omoleyin MacArthur ang-yi Sheu (xu Fang yi ) - ogbontarigi onijo fun ile-ise Martha Graham at atilan M’’ Lanma Lan bu lai dun dun lu lu luly Mama - Aogo - Aat Soana - Areti Chiang ( Areti Wel G (jíà Wwen Lan ( A Soana Chiang (Jiang W Kwara G ) - ati elere tíátà David 1990 (Z FM In Adein Adeight gbogbo okan lara Olugbe Nigba Oni-iṣẹ Onilola Diana eng - Aogo Joe M - Aosu Soori Oriman Ni osu agbo India ati gbajú Jonathan to ati gbajú ati gbajú onisowo Derek - Aso Ni N Aosu So ati Iya ati olorin ati olorin ati olorin | Iya | ati olorin FM (agbo N ati Hi Anna (Xia & - Aosu Sowe (Tan Wana (Tan yan * * *N osu N Ade W (W WW (W - A ati 20 ka osu Ogun Ala W W WW We W ) - Aosu So (wu (wu akoko - A A osu Z - oludari I-Ona To Olu tun*_
wikipedia
yo
Zhang ying ) - òǹkọ̀wé Kang-i Sun Chang (Sun Kang yí ) - ÒǸKỌ̀WÉ and ati onimo Litireso Lan Samantha Chan - onkọ̀wé; oludari Iowa writer's Work Victoria Chan – Nirònú, onkowe awon omo omo Menaroko Ted Chiang (Jiang ff Fone ) - On itan Seri * Frank Chinz (Z Alund Xiu ) - ònkọ̀tàn, on ere-ONÍṢẸ́, ati Karoko Marilyn Chinchen (chen 2016 Ling ) - Akéwì ben G (Zhang Hen Tangta Yunmu ] - Onkọ̀wé ati adari awon oṣiṣẹ David Henry San Monwa (Huang Lunda ) - On Ere-ONÍṢẸ́ O- iwe gi (Ren Bi lian ) - Onroko, ònkọ̀tàn Ha Ha (Ha Ha Jin ( ònkọ̀tàn, oun lo gba ami-eye National National Book fún Waiting Fún 1980 Kingston - ònkọ̀tàn Iwe The Woman Wa Wa R..
wikipedia
yo
Kuang (Kuang Lingling Xiu ) - ònkọ̀tàn méèri ayanilẹ́nu, The Poppy War Jean Kitan - ònkọ̀wé, ònkọ̀tàn Edward Michael Law-Yone - ÒǸKỌ̀WÉ, oníṣẹ́ ìròyìn; bàbá Wendy Law-Y Wendy Law- - ònkọ̀wé gus Lee (Li Alund Sún ) - Onkọ̀wé Carolyn Le-lani -O ònkọ̀wé Yves Li (Li Yi Guv ) - Ẹni tí ó gba ami-ẹ̀yẹ Pen/ from lọ́dún ed lin (lin (Lin NAN ) - Onkọ̀wé, onkọ̀wé àkọ́kọ́ tó gba ami-ẹ̀yẹ Asian American Literary Awards ní ẹ̀mẹ́ta Tao Lin (lin (lin = ▪ Òǹkọ̀wé Eric Liu (Liu Bo Chuan ) - Onkọ̀wé àti Akọ̀wé-ètò fún Ààrẹ [ Amẹ́ríkà, Bill Clinton Malinda lo - ònkọ̀wé Ìtàn Ìtàn, Ash Wong Lo Lou ( zu WE WE (i Òǹkọ̀wé Marie Marie lu X wé X) - On Adeline Adeline Àlàáfíà (ma yán Junling Ling ) - Onkọ̀wé àti Oníṣẹ́ Ìlera William Williamr (Ma Nwe (i yí,i ma ga ) - Onímọ̀ Ẹ̀rọ, Airo Ogbu, ati Òṣèréètò An] ati Òṣèréd Vin Mid Oroko Red Red A Cele ng Cele (O ÒKÈ ) - Ondọ́gba Okọ̀tàn Lisa Lisa Alufaa tòótọ́ sin Far (Shuan X Huka _*) - Òǹkọ̀wé àti Oníròyìn Amy tàn ( en 2016 ) - On the Joy Ju Club Timothy Tau (E Ibit ( O- Okọ̀tàn, ònkọ̀tàn, Olùdarí eré àti Akọ̀wé Eré Eré..
wikipedia
yo
jáde Snow Wong (Huang Yu XUv ) – Òǹkọ̀wé Shawn Wong - ònkọ̀tàn Ìwé Homebase, American Knees; ònkọ̀wé; Ọ̀jọ̀gbọ́n Timothy C..
wikipedia
yo
Pepe (Bebe yu from ) - ayaworan Ekole, ti o ya aworan Ekole ile Louvre pyramid Omi so - ayaworan ohun eso May Sun - elere fan thunpi - ayaworan, Infingba Frank Wong - elere di TY OME Wong (Huang Yaọ ) - elere Frank wu - Onimọ Oni Bawo Seriri XU Bing - elere - itọkasi..
wikipedia
yo
Yunifásítì ìlú Paris-saClay (tàbí Yunifásítì Paris-saClay, ) jẹ́ Yunifásítì kan ní ìlú Gíf-sur-Yvette, Fránsì..
wikipedia
yo
Upsa ti wà ní àìyẹsẹ̀ ní ipò nínú àwọn tí ó dára ju ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ ní ayéàwọn ìtọ́kasí àwọn yunifásítì..
wikipedia
yo
xu Qing (; tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìlélógún osù kìíní ọdún 1969), tí a tún mọ̀ sí Summer Qing, jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin ọmọ China..
wikipedia
yo
Wọ́n gbà á sí ilé-ẹ̀kọ́ sinimá Beijing Film Academy lọ́dún 1988, ó sìn kẹ́kọ̀ọ́ jáde lọ́dún 1992.Iṣẹ́ọdún 1999 ni Xu kọ́kọ́ jáde nínú sinimá kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ made life on a string, tí chen Kaige dari..
wikipedia
yo
Wọ́n yàn án lọ́dún 1992 fún àmì-ẹ̀yẹ hundred Flowers Award for Best Actress nítorí ipa tó kó nínú sinimá Ripples Across Stagnant Water..
wikipedia
yo
Lọ́dún kan náà, ó tún di ìlúmọ̀ọ́ká sì ní gbogbo China nínú eré orí tẹlifísàn kan tí wọ́n ń pè ní At The Foot of the Imperial City lọ́dún 2001, ó tẹ̀ síwájú nínú iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn tó kópa nínú eré Ren yingying tí wọ́n máa ń ṣàfihàn lórí tẹlifísàn, Laughing in the wind (2001).Lọ́dún 2003, Xu gbàmí-ẹ̀yẹ Audience's choice for Actress ní China TV Golden Eagle Award fún ipa tó kó nínú sinimá kan tí ó ti kópa gẹ́gẹ́ bí Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́, the Chinese woman at the Gunpoint of Gestapo.Lọ́dún 2009, Xu kópa gẹ́gẹ́ bí Soong Ching-ling nínú sinimá ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ àwọn China tí wọ́n pè ní The Olùding of a Republic,, sinimá yìí ló mú un gba àmì-ẹ̀yẹ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tó dára jù lọ ní MCaul International Movie Festival àti hundred Frs Awards..
wikipedia
yo
Ní ọgbọ̀n ọjọ́, Oṣù kọkànlá ọdún 2009, wọ́n gba xu gẹ́gẹ́ òṣèré fún fún ètò ìràwọ̀ HuAyíta Brothers.Lọ́dún 2010, ó tún ṣe dáadáa nínu sinimá ìfẹ́ kan tí wọ́n pè ní Blos of Beautiful Flowers, tí gao Xxi..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2012, ó kópa gẹ́gẹ́ bí ìyàwó Bruce Willis nínú sinimá Amẹ́ríkà tí wọ́n pè ní Looper.Lọ́dún 2013, Xu gba àmì-ẹ̀yẹ Huth Awards gẹ́gẹ́ bi òṣèrébìnrin tó dára jù lọ nítorí ipa tó kó nínu eré orí-ìtàgé tí wọ́n pè ní a Dream Like a Dream.Lọ́dún 2016, Xu tún di gbajúmọ̀ sí i nínu sinimá ọ̀ràn dídá kan tí wọ́n pè ní Mr..
wikipedia
yo
Six, which won her the hundred flowers award for best Actress award.Lọ́dún 2017, Xu tún gbajúmọ̀ sí i ninu ògbójú sinimá gúúsù Amẹ́ríkà àti Afirika tí wọ́n pè ní 24 hours to live.Àtòjọ àwọn sinimá rẹ̀sinima orí fífíàwọn àmì-ẹ̀yẹ tó gbà àti èyí tí wọ́n yàn án fúnàwọn itọkasiàwọn ará ṢÁÍNÀ..
wikipedia
yo
Àwọn ilé-iṣẹ́ ìpínlẹ̀ China tí wọ́n ṣe ọkọ̀ ojú-omi akérò ní ilẹ̀ China tí a mọ̀ sí (CSSc) ní ó jẹ́ ilé iṣẹ́ aláfọwọ́ sowọ́pọ̀ tí wọ́n ń kó ọkọ̀ ojú-omi akérò ní ilẹ̀ China.àgbékalẹ̀ RecSS ní ó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn ẹ̀ka mẹ́wàá nílé ìṣe ọmọ ogun ní orílẹ̀-èdè China, ní ó ní ayé Igbókó ojú-omi sí, ó ní oríṣiríṣi irinṣẹ́ tí wọ́n fi ń ṣe ọkọ̀ ojú-omi tuntun yálà ti àwọn ọmọ ogun ní tàbí ti ikérò lásán..
wikipedia
yo
Wọ́n gbé díẹ̀ lára àwọn ilé-iṣẹ́ kékèké tí ó wà lábẹ́ àjọ wọn bíi CSSc Holdings Limited sí Ọjà Owówó ti Shangai, tí wọ́n sì tún ti ara ibẹ̀ rí àwọn ilé-iṣẹ́ Shangai wàigbàndiọ Shipbuilding sí abẹ́ àkóso wọn.Ìtàn ni Sobakíbi wọ́n ṣe bẹ̀rẹ̀ní ọdún 1964, wọ́n dá ilé-iṣẹ́ sixth Ministry of Machine Building sílẹ̀ láti lè ma fi ṣàkóso gbogbo àwọn ilé-iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣe ọkọ̀ ojú-omi jáde ní ilẹ̀ China, tí ó sì jẹ́ wípé gbogbo ọkọ wọn tí wọ́n ń ṣe jáde ni ó jẹ́ ti àwọn jagun-jagun..
wikipedia
yo
In July 1982, wọ́n dá ilé-iṣẹ́ yí sílẹ̀ láti fi ṣe àtúntò sí ilé-iṣẹ́ ọmọ ogun ilẹ̀ China ni, tí wọ́n sì ṣe àyípadà rẹ̀ sí China State ShipBilding Cooperation..
wikipedia
yo
Àjọ CSSc yí wà lábẹ́ ìṣàkóso ìpínlẹ̀ àmọ́ wọ́n fún wọn ní àǹfàní láti má ṣiṣẹ́ kí ìdàgbà-sókè ó lè bá ọrọ̀ ajé orílẹ̀-èdè wọn..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1992, àjọ CSSc yí àfojúsùn wọn padà sí wọn ma ṣe ohun tí tẹrú-tọmọ ó lè lo ní orílẹ̀-èdè China, tí ida ọgbaorin nínú ohun tí wọ́n ń pèsè jáde ṣe jẹ́ ohun tí àwọn ará ìlú le jànta rẹ̀..
wikipedia
yo
ìgbà tí yóò fi di ọdún 1993, wọ́n ti n ta ìlàjì nínú àwọn ohun tí wọ́n n pèsè sí ilẹ̀ òkèrè.Àyípadà tí ó dé bá Cccníparí ọdún 1990, ṣíṣàtúntò tí wọ́n lọ́dún ètò ọrọ̀-ajé orílẹ̀-èdè China mú kí ìjẹ gàba ilé-iṣẹ́ àwọn kánrin kánrin ènìyàn tí wọ́n lẹ́nu lóró ó fọ́ka yangàn, tí àwọn oríṣiríṣi aládàáni tí wọ́n jẹ́ mẹ̀kúnù náà ó bẹ̀rẹ̀ sí ń dá sí pípèsè nkan oríṣiríṣi jáde láti lè mú kí ìta-kan ó wáyé níbí pípèsè nkan jáde ní orílẹ̀-èdè China..
wikipedia
yo
Nigba o di inu osu keje odun 1999, won yo China Shipbuilding Industry Corporation kuro lara ajo CSSc; ti won si pin awon ile-ise agbaoko-jade si ẹkùn o HEL, amo ti CSS se n dari gbogbo won paa paa julo ni apa ariwa ati aarin gbùngbùn ile China..
wikipedia
yo
Àjọ CSSc Náà tún ń jábọ̀ fún Ẹ̀ka Ọba ti State-Irú] àjèjìts Supervision and Adno Commission (Ṣàṣà).Ẹ tún lè wo àwọn àyọkà wọ̀nyíhu Chugnhi, former CEO of the CSSstst of largest shipyard ìtọ́ka síàwọn orísunàwọn àsopọ̀ itaChina State Shipbuilding Corporation (CSSc)China) CSS Hols limitedvehihicle manufacturing companies established in 1999government-3] Companies of Chinheadbuilding companies of Chinamanufameric companies based in BeijingChinese Brandefence companies of the People's Republic of Chinveseese companies established in 1999..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí ètò ìkànìyàn the sixth population Census ẹlẹ́kẹfà irú rẹ̀ ti sọ ní ọdún 2010, àpapọ̀ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n kàwé ní ìrilẹ̀-èdè Chinàjẹ́ 95.9..
wikipedia
yo
Àmọ́ iye àwọn tí wọ́n kàwé ní ẹkùn-o-ọpẹ́yágágá ni wọ́n yà tó ṣíra WỌN..
wikipedia
yo
Awon eleyi ni won wa ni ipele anoko ninu isejoba ti eto ikaniyan gbe jade , ti o fi mo awon ẹkùn kookan ati agbegbe bi won se tele ara won ninu ipo isejoba lati ori omo odun mẹ́ẹ̀ẹ́dogún soke bi eto ikaniyan orile orile-ede (Bureau of statistics of the pRC.) China se se akosile re ni odun 2010 teaarin gbùngbùn ChinAhong geesi ati maCauàsopọ̀ itanBO Bureau of Statisticllisi Stadinteracy rateilcycy rateracy, ilwcycy rate..
wikipedia
yo
Project 211 () ni wọ́n bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 1995 tí ó jẹ́ iṣẹ́ àkànṣe ti Obda lórí awo Fásitì tí wọ́n ṣe pàtàkì ní orílẹ̀-èdè China lábẹ́ àjọ tí ó bojútó ètò ẹ̀kọ́ lábẹ́lé..
wikipedia
yo
Wọ́n dá iṣẹ́ àkànṣe yí sílẹ̀ láti lè fi ẹsẹ̀ iṣẹ́ ìwádí tó peregedé múlẹ̀ kí wọ́n sì wá àwọn ọ̀nà tó yanrantí fún ìdàgbà-sókè àwùjọ..
wikipedia
yo
Nígbà tí wọ́n kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ rẹ̀, láàrin ọdún 1996 sí ọdún 2000, iye owó tí wọ́n ṣàmúlò lápapọ̀ jẹ́ bílíọ̀nù meji dọ́là.Nígbà tí yóó fi di ọdún 2008, orílẹ̀-èdè China ti ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì tí ó ti tó 116 nígbà tí ida mẹ́fà nínú àwọn ilé-ẹ̀kọ́ náà ti wà ní ipò tí wọ́n fẹ̀ gan an..
wikipedia
yo
Project 11 mú kíkọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀ ìwòsàn onípele kejì àti onípele kẹ́ta lọ sí ìlú òkèrè láti lọ kọ́ nípa ìmọ̀ náà síwájú sí..
wikipedia
yo
Gbogbo Fásitì ti wó ṣugbà ètò yí jẹ́ ọgọ́rùn ún kan.Láti ọdún 2014, Project 211 ni wọ́n ti ń ṣàtò sí tí wọ́n sì ti fi iṣẹ́ẹ àkànṣe míràn tí wọ́n pè ní Plan 111 tí yóò ma ṣe àfikún ọgbọ̀n orí àti ìwà ọmọlúàbí kún iṣẹ́ àkànṣe náà.Nínú oṣù kẹsàn án ọdún 2017, wọ́n tún ṣe àgbékalẹ̀ iṣẹ́ àkànṣe míràn tí wọ́n pè ní double first class University Plan was announced..
wikipedia
yo
Àgbékalẹ̀ tuntun yí kò fi bẹ́ẹ̀ yẹ àjọ tí wọ́n rí sí ipò tí àwọn Fásitì kọ̀ọ̀kan wà lágbàáyé bí wọ́n ṣe le ṣe ìgbéléwọ̀n fún wọn..
wikipedia
yo
Liu yanDong (; tí wọ́n bí ní ọjọ́ méjìlélógún oṣù Kọkànlá ọdún 1945 ne olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè China tí ó ti fìgbà kan tẹ́lẹ̀ rí jẹ́ igbákejì Olórí orílẹ̀-èdè China tẹ́lẹ̀ rí, ó sì jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú Politbu of the Communist Party of China láàrin ọdún 2007 sí 2017, ó sì tún jẹ́ àbójútó ní ìpínlẹ̀ kan ní orílẹ̀-èdè China, bá kan náà ni ó tún adarí fún ilé-iṣẹ́ United Front Work Department lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú comminuty láàrin ọdún 2002 sí 2007.Gílíádì ni ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ilé-ẹ̀kọ́ tsing University, ni ó sì ti ń ṣiṣẹ́ ribiribi fún ilé-ẹ̀kọ́ náà gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ̀ọ́ jáde lábẹ́ ẹgbẹ́ Communist Youth League hù hù Jint, fún èyí, ìwé ìròyìn kan tilẹ̀ ṣe àpèjúwe Liu gẹ́gẹ́ bí “an “Ahenan ní èdè China, tàbí “Youth League Clique" ní èdè Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Liu ni wọ́n tún mọ̀ gẹ́gẹ́ bí gbajú-gbajà obìnrin olóṣèlú lẹ́yìn tí arábìnrin wú yí, ti fẹ̀yìn tì gẹ́gẹ́ bí olódálúlú ní orílẹ̀-èdè China.Ìbẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ olódáọlọ̀tẹ̀ yánṢàánú ni wọ́n bí ní agbègbè NANg, ní Jiangsu tí ó jẹ́ olú-ìlú fún orílẹ̀-èdè China nígbà náà..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ Liu Ruilo ni ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùdásílẹ̀ 14th army of the rẹ̀dṣ’’, àwọn ọmọ ogun tí wọ́n da sílẹ̀ láti fi ìjíjà-n-gbara..
wikipedia
yo
Àwọn ènìyàn ma ń bu ọlá fún yanṢàánú látàrí wípé bàbá rẹ jẹ́ ọ̀kan gbòógì lára àwọn tí àwọn jà ígbara fún orílẹ̀-èdè èdè China, lọ́pọ̀ ìgbà, wọ́n ma ń tọ́ka sí Liu gẹ́gẹ́ bí Princeling..
wikipedia
yo
Liu wo ilé ẹ̀kọ́ tsinga University ní ọdún 1964,tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ọdún 1970 gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ ìṣègùn..
wikipedia
yo
Ní àsìkò tí ó wà ní akẹ́kọ̀ọ́ nílé ẹ̀kọ́, ó wà lára àwọn tí wọ́n kọ́ àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ nípa ẹ̀kọ́ ìṣèlú..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè, ó bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ onímọ̀ ìpoògùn ní ìlú Tanghan..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1980, wọ́n gbé lọ láti lọ ṣiṣẹ́ fún ẹgbẹ́ òṣèlú kan ní ìlú Beijing, wọ́n sì fi ṣe igbá kejì olórí ẹgbẹ́ ọ̀hún ní ọdún 1981, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣiṣẹ́ fún ẹgbẹ́ Communist Youth League ní ọdún 1982 níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ kan WW ZhaOgu, hù Jint, àti Song Dé..
wikipedia
yo
Ó Ṣiṣẹ́ Pẹ̀lú Youth League fún odidi ọdún mẹsan an gbáko..
wikipedia
yo
During this time she served as Chairwoman of the all-China youth Federation.Nígbà tí ó di inú oṣù kẹta 9d7n 1991, Liu bẹ̀rẹ̀ sí ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú United front Work Department gẹ́gẹ́ bí igbá kejì akọ̀wé àgbà..
wikipedia
yo
Ẹnu iṣẹ́ẹ yí ni ó wà tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ọ̀mọ̀wé àti ọ̀jọ̀gbọ́n ní ilé ẹ̀kọ́ Renmin University àti Jilin University.Iṣẹ́ rẹ̀ ní United Front Workláàrin ọdún 2002 sí 2007, ó ṣiṣẹ́ ngẹ́gẹ́ bí adarí United Front Work, wọ́n sì yàn án sípò ìgbà kejì Alága ẹgbẹ́ òṣèlú Chinese People’s Political consultative Conference..
wikipedia
yo
Látàrí wípé ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú akọ̀wé àgbà àgbà ẹgbẹ́ náà, ìyẹn hu Kilt, àti ipa ribiribi tí ó ti kó nínú Communist Youth League, ó wọ inú ẹgbẹ́ òṣèlú Politbu of the Communist Party of China ní ọdún 2007..
wikipedia
yo
Dídára pọ̀ tí ó dára pọ̀ mọ́ ẹ̀gbẹ́ yí ni wọ́n ti ń fojú sùn ún wípé ó lè di igbákejì aṣojú ẹkùn rẹ̀..
wikipedia
yo
Liu ni ó e obìnrin olóṣèlú kan ṣoṣo tí ó fẹsẹ̀ múlẹ̀ jùlọ tí ó sì ṣe é ṣe kí ó dé ipò Politbu''' tí ó jẹ́ ipò ìṣèlú tí ó ga jùlọ nílẹ̀ China..
wikipedia
yo
Ní àsìkò ìdìbò, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí igbákejì sí ipò state Council, lábẹ́ ẹ̀gbẹ́ ìṣèlú ..
wikipedia
yo
Oun naa tun ni won fi se igba keji Alaga Beijing Organizing Committee for the Olympic Games.Ìgbé ayé reliu se igbeyawo ni ojo ketala osu kerin odun 2009, ile-eko STony Brook University fi ami-eye Doctor of Laws da arabinrin Liu lola.Ẹ tun le wo tsing Clíque Oritoka síàwọn ìtàkùn Idde Dise Profile of Liu yan In)".A News News.
wikipedia
yo
Biography siikia (November 2012)Àwọn ènìyàn Alààyèàwọn Ọjọ́ìbí ní 1945 From Nantour·s Republic of China politicians from Jiangsu Communist party politicians from Jiangsu PreOnídàájọ́ls of the People's Republic of China Chair Oludarapersons of National Committee of the Chinese People’s Political Olùmíràn Conference of the 18tht Polit of the Chinese Communist party Ibitsing University Ibimírànsts From Women Women in Politics Olu 1992 of ChinÉlì of Chinclusi of the 17th Polit of the Chinese Communist party-ọlà Women Poli..
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe ìfilọ́lẹ̀ ibùdó ìgbafẹ́ ti ìjọba àpapọ̀ ní orílẹ̀-èdè China ní ọdún 2013 níbi ìpàdé Pperry session of the 18th Central Committee of the Communist Party of China ẹlẹ́kẹ́ta irú rẹ̀..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó di ọdún 2016, wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ ibùdó ìgbafẹ́ etí omi tàbí odò three-River-source National Park gẹ́gẹ́ bí àyẹ̀wò fún iṣẹ́ àkànṣe náà..
wikipedia
yo
Ọdún yí náà ni wọ́n dá ibùdó ìgbafẹ́ fujian wuyì Mountains National Park sílẹ̀, lẹ́yìn àwọn wọ̀nyí, oríṣiríṣi ibùdó ìgbafẹ́ bíi mẹ́jọ ni wọ́n tún ti dá sílẹ̀..
wikipedia
yo
lọwộ lọwọ bayi,awọn ibudo igba ti o wa ni orilẹ-ede China lasiko ti a n ke apileko yi ti to mọkanla ti gbogbo wọn si wa labẹ akoso ile-iṣẹ ijọba National Fiturstry and grassland Administration.Àwọn ibudo ìgbafẹ́ naa nìwọ̀nyíe tun le wolist of National Parksprotected areas of Chinire itọka si National ParkhinJóòbù Heritage of Chinap Eluted areas of Chinìpèsè..
wikipedia
yo
Èyíb ni àtòjọ orúkọ àwọn akéwì lèdè Chinai Qinï Juyi tàbí bọ́ Juyi Banv Guó (32 a Orílẹ̀d Oyè Be Lince Zhi La Olùṣọ́ Wén E Y Mi O 2 2 2 Al Pi Pi [2] Cenka Cenka Lo Fi Orúkọ Lo Fi Fr Olùdi Kan M - rín (3] Mo Japan 2 kọ́ ewì Ìró China, ògbóǹtarìgì Onímọ̀ Lítíréṣọ̀ Ọmọ Japan tí Ó kọ ewì China Ma Japan Mo Mo O https Aged poet O N O W Wa O N Tuntun Olù Olù Olùbù “The “The “ Olù Tuntun (80- ] AKÉWÌ " Official 0 du O D 2 U Mo La * Mo * F níbẹ̀, O Mi Mi https Robert V Mo Z Guce Guce Gu Gu Ma Gu Guce * O. Mo K
wikipedia
yo
Àwọn wọ̀nyí ní àtòjọ àwọn òǹkọ̀wé-bìnrin ọmọ China.BIgbasort Ban ©
wikipedia
yo
Mánásè ce) akéwi Anni baọbẹi (born 1974) onkòwé ìtàn Bing )". (1900-1999) onkòwé ìtàn méẹ̀ríri àti ìwé ọmọlé.ai yán (C..
wikipedia
yo
178 – Post 206) Akéwì Chang Chl'Ho (1914–2015) Akéwì Eileen Chan (1920-1995) ònkọ̀tàn, Aroko..
wikipedia
yo
chen Kugrong (1917-1989) AKÉWÌ Chen Danyan (born 1958) ònkọ̀wé nípa ìgbésí ayé ènìyàn chen XUäce (1906-1991) ònkọ̀wé àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀Angélica Chelung (born 1966) onkòwé ẹ̀ṣọ́ìdájù houʹtos (1938–1996) Nolonwekòwé ìtàn Arosọ ding Ling (1904-1986) onkọ̀wé itan aroso duan Shuqing (C..
wikipedia
yo
A1600) akewiff angang (born 1955) akewi ati ònkọ̀tàn bú Fèiyan (born 1981) ònkọ̀tàn ff China- (1900-1974) Fu Shanxiang (1833-1864) Ọ̀mọ̀wé fu Olùan (born 1946) Klara yu (born 1944) oníròyìn Gu Taiqing (1799 - C..
wikipedia
yo
1877) akewi Guan 0b013eheng (1262–13) akewih jing Coang (born 1984) ònkọ̀tàn Hong ying (born 1962) ònkọ̀tàn àti ìyáàrin Ganggang Hu Guidice (born 1984) onkòwé àti òṣèrébìnrin Huqi Lanqi (1994-1994) ònkọ̀wé Ọ̀gágun Huang E (Mon- AKÉWÌ Madame Huáru N (C..
wikipedia
yo
940-97) Akéwì 107 Biwe (1899-1978) akọ̀wé ÌrántíKikeke yan (1929–2011) akọ̀wé eré-oníṣe, ònkọ̀tàn àti Akey Qingzo (1084 - C..
wikipedia
yo
1151) ònkọ̀wé àti olùrà yé (Ó kú ní Jorín) Kyáàang Dsheng (17–1847-1847) AKÉWÌ àti ònkọ̀wélin Huiyìn (1904-1955) asọ̀tàn ohun-àlúmọ́nì Lin Zong (1878-1944) Aroko nípa ètò àwọn obìnrin Ling Shuhua (1900-1990) akọ̀wé ìtàn ìgbàlódé àti oníṣẹ́ ọ̀nà Liu RShishi (1618-16) AKÉWÌ Liu ying (born 1974) ònkọ̀tàn lu BCheng (1883-1943) AKÉWÌ àti sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀ Luo Luo (born 1982) ònkọ̀tàn Luq Kou Kouse (born 1969) Onimi Mian (born 1970) on ìtàn arorún Pan (born 1945) on Irin-FM Hu-FM Mi-W-1907) AKÉWÌ, Aroko àti onkọ̀wé nípa Òrated OyOmane (won (won bi ní 1972) ònkọ̀tàn sọ́bàál, 20 àti onílẹ̀ Oz Zz (1925- 20- Oroko V' (C' (C.. ( Ofo ( Oòótọ́ (2] Ìrìnkèrindò ( Okò ní eré V (mita Mo ní A R2 ( May Aroko (1] on ( Nori (os Kan (born Mo Ch O Tuntun ( Ka & AWAMO (born el K (2 PA A 2017- OyO O (FM 2017- Aroko (2] N Li O (ii 2008- N Akọ̀wé O Olù (FM Mo Awo Mi ( Ka (born A Tuntun (4] N Tuntun ( O kú (FM _*(2 Ka A O (17 W Mi O Kan O Mi Mi Mi Mi (FM O O (17 Of A [FM _*Mi - O FM Mo N Kan Mi _*ní O R O To Mi Mi (e O (FM The
wikipedia
yo
Adam-ibo) akewi ati onkọweShen Qing (Living) onkọwe nipa eso Shen Rong (born 1936) ònkọ̀tàn AroShen Shaniba (1808-1862) akewi ati ònkọ̀tàn Shu Gting (born 1952) akewi Su Hul AKÉWÌ Su Qing (1914–1982) akotan Su Xiao (C..
wikipedia
yo
501) Akéwì ṣu X’’Elin (1897-1999) onkọ̀wé àti Ọ̀mọ̀wéttian China (born 1985) akọrin, akọ̀wé àti òǹkọ̀wé Ning (born 1957) ònkọ̀tàn àti ònkọ̀tàn wẹ́wẹ́wwang QingHul (12–12-12) Akéwì Valdecilla (won bi lọ́dún 1954) Fiction writerdojúkọ Wei (15–Tgaines) akewi WW XUfàádọ́jọ (won bi lodun 1955) onkọ̀wé nípa ohun mimu, tii ati ònkọ̀tàn WW Yun (1749-1819) AKÉWÌ ati Akowe Ere-ONÍṢẸ́ Wyun WW (won bi ni odun 1964) akewiwo eserr (won bi ni lodun 1966) Blog, poet and Iweyi Kant Mot bi 2016 bi 2016) on nipa àwùjọ O wu za- Oroko) Kkarun-X) May Mo bi Mo bi onwù onkowe ati akewi (won bi 2016 bi 2016) on aro nipa ti itan ati itan mẹ́ẹ̀l Mo ọjọ́un (1911-1942) ònkọ̀tàn (2] ònkọ̀tàne (1906 (1906-2000) ònkọ̀tàn nipa awon eniyan Xe da Nita Ni Omo Wailales xu (13) (13-2] (2] (FM S
wikipedia
yo
BCE) poetxu Hul (6–650) AKÉWÌ XU kún (born 1965) PostModern Fiction writerxu Zhua (1873-1935) AKÉWÌ XUE ṣùṣù ©
wikipedia
yo
1650) Akéwì XUe Tao (bẹ́rẹ́-831) Akéwì D)". (born 1958) akotanyyang erche námù (won bi lodun 1966) onkòwé nípa àwùjọyang Gang (1905-1957) oníròyìn, ònkọ̀tàn àti Aṣọgbu Yang Hongying (won bi lodun 1962) Children's Fiction writeryang Jiang (1911-2016) akọ̀wé eré-oníṣe, ònkọ̀tàn àti Aṣọgbuting- yé (won bi lọ́dún 1952) Author of Young adult novelsye yinghun (born 1970) Intatorator-taying Yeh (born 1924) akéwì àti Ọ̀mọ̀wé Yu XUu (C..
wikipedia
yo
868) Akéwì.oríal Yong (won bí LỌ́DÚN 1955) Akéwì lijíà Zhang (wọ́n bí lọ́dún 1964) sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀zeng BaOsun (1893-1978) ònkọ̀tàn Zhang Hidi (won bi lọ́dún 1955) akewi àti àsọgbuon Zhang Jie (won bi lodun 1937) ònkọ̀tàn Zhang Kangkang (wọ́n bí lọ́dún 1950) ònkọ̀tàn Zhang Ling (wọ́n bí lọ́dún 1957) ònkọ̀tàn Zhang )".82 (Wọ́n bí Lọ́dún 1953) ònkọ̀tàn nípa ìgbésí ayé ènìyàn àti ònkọ̀tàn Zhang Yotió (Fl..
wikipedia
yo
ce) Akéwì Zhang Yuẹran (wọ́n bí lọ́dún 1982) ònkọ̀tàn Empress Zhangsún (601-636) Aroko Zhao Luanluan (Flrs..
wikipedia
yo
ce) akéwi Zhao Luòrui (1912-1998) akéwi Aṣọgbuon Zheng Min (won bi lodun 1920) omowe ati akéwi Zheng yunduan (C..
wikipedia
yo
1327–13– poetyilinlin ZHong (Living) Fiction writer and Poetzhou Wehui (won bi lodun 1973) ònkọ̀tànzong pu (Wọ́n bi Lọ́dún 1928) ònkọ̀wé àti ọ̀mọ̀wé Zhu lin (born 1949) ònkọ̀tàn Zhu Shuhen ©
wikipedia
yo
Ìyálóde jẹ́ obìnrin onípò gíga nínú ọ̀pọ̀ àwọn ìlú ìbílẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Lóde òní, àwọn ọba ló ń fi obìnrin joyè Ìyálóde, àmọ́ lọ́dún 2002 Njoku ṣàlàyé pé láyé àtijọ́ nílẹ̀ Yorùbá, ìlànà ìyannisípò gẹ́gẹ́ bí Ìyálóde kò jẹ mọ́ ìpinnu ọba..
wikipedia
yo
Kàkà bẹ́ẹ̀, yálà a ó fi obìnrin joyè ìyálóde tàbí bẹ́ẹ̀ kọ́, dá lórí àṣeyọrí àti ìkópa nínú ìgbòkègbodò — ìyẹn ló mú wa bọlá fún un pàápàá tó bá dọ̀ràn ọ̀rọ̀ ajé àti ìṣèlú.Ìtàn nítorí náà, nínú ìtàn, kì í wulẹ̀ ṣe pé Ìyálóde ń ṣojú fáwọn obìnrin ní àjọ ìgbìmọ̀, ṣùgbọ́n ó tún jẹ́ ọ̀kan lára olùdarí ìṣèlú àti ọ̀rọ̀ ajé ní ìjọba ìbílẹ̀ Yorùbá.Nínú ìtàn àròsọ Yorùbá, a tọ́ka sí i gẹ́gẹ́ bí “ọba obìnrin”, àbá Ìyálóde ni ìjòyè máa ń jíròrò nípa ní Ìgbìmọ̀..
wikipedia
yo
Lọ́dún 2017, Ọlátúnjí ti Yunifásítì Tai soláàrin fi ojúṣe Ìyálóde wé ojú ìwòye Ìṣègbèfábo lóde òní..
wikipedia
yo
Ó wá ṣàlàyé pé Ìyálóde ti ọ̀rúndún kọkàndínlógún, Ìyálóde Tinúbú, jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n lọ́rọ̀ jù nílẹ̀ Yorùbá, ó sì kópa pàtàkì nínú ìpinnu ẹni tí yóò jọba nílùú méjèèjì Èkó - ibi tí ó fẹ́ ọba - àti nílẹ̀ Ẹ̀gbá - ibi tí ó ṣètìlẹ́yìn fún àwọn Ẹ̀gbá ẹlẹ́yà rẹ̀ nígbà ogun..
wikipedia
yo
Modomi sọ pé ipa tí Ìyálóde kó, kò mọ sọ́dọ̀ àwọn obìnrin nìkan, ṣùgbọ́n ó tún ní í ṣe pẹ̀lú gbogbo ìṣèlú, àṣà àti ẹ̀sìn Yorùbá..
wikipedia
yo
Ó mẹ́nu kan Tinúbú àti Ẹfúnṣetán Aníwúrà bí àpẹẹrẹ tó hàn gbangba..
wikipedia
yo
Ṣófo (1991) jẹ́rìí sí ọ̀rọ̀ yìí, ní sísọ pé “Bó ti wù kí ọba lágbára tó, kò lè gbapò Ìyálóde láéláé”
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọlápó ṣe sọ, àṣẹ tí Ìyálóde pa lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà lóde òní ó pọ̀ bí i ti tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Aláàfin Ọ̀yọ́, Làdi Adéyẹmí, tọ́ka sí ìparun àṣà tìtorí àṣà “ìgbàlódé” gẹ́gẹ́ bí èrèdí ìṣẹ̀lẹ̀ náà..
wikipedia
yo
Ó rántí pé láàárín àwọn ìgbìmọ̀ olùdarí, àwọn obìnrin ní ipò pàtàkì tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀..
wikipedia
yo
Bí àpẹẹrẹ, wọ́n ní Tinúbú lẹ́nu láwùjọ tó bẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́ tí ó dá ọba ìlú Èkó dúró kó má ṣe fi Èkó lé àwọn Gẹ̀ẹ́sì lọ́wọ́ fún ìgbà díẹ̀.Ìyálóde ìsinsìnyí olóyè bábá Lawson ni Ìyálóde ilẹ̀ Yorùbá nísinsìnyí, Aláàfin Ọ̀yọ́ ló fi í joyè yìí lọ́dún 2008..
wikipedia
yo
ṣáájú ìyẹn, Ìyálóde ilẹ̀ Ẹ̀gbá ni.Àwọn ìtọ́kasí obìnrin ní nàìjíríàìṣèlú Yorùbáíko oyèìṣèlú..
wikipedia
yo
A bí Olumide Mkanjuola ní Ọjọ́ keje Oṣù Kẹfà Ọdún..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó sì tún jẹ́ a jà fún ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn..
wikipedia
yo
On s'Otan ni, bakanna lo si je agbejoro fun agbekale ti a n pe ni LGBTQI ati gbajugbaja olóko..
wikipedia
yo
Òun ni Olùdarí àgbà fún The Initiative for Sper Rights (jẹun), Ilé Iṣẹ́ yìí ló ń jà fún ìṣe déédé nínú ètò ènìyàn láwùjọ àti pé lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, òun ni olùdarí ètò fún Initiative Sàǹkòfà d'Afrique de l'oú (iṣPAyo) tí ó jẹ́ ilé-iṣẹ́ ní agbègbè ti Faransé ní Áfríkà tó ṣe àdúrótì fún àwọn ẹgbẹ́ tó ń ṣe agbátẹrù àti àtìlẹ́yìn fún àwùjọ tí kò ní ìwà ipá àti ìrẹ́nijẹ láàrin gbogbo àwọn ará ìlú, wọ́n ṣe èyí pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ owó fún àwọn irúfẹ́ ilé-iṣẹ́ báyìí ní orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan.Ní ọdún 2016, Makanjuola gba àmì ẹ̀yẹ ọba'bìnrin fún àwọn ọ̀dọ́ tó wà ní ipò asas (Queen’s Young Leaders Award) lórí iṣẹ́ rẹ̀ láàrin LGBTI pẹ̀lú àwọn agbègbè/àdúgbò, òun sì ni ó gba àmì ẹ̀yẹ fún ẹni tí ó yẹ fún ọjọ́ ọ̀la ní ọdún 2012 ní ipò ẹni tí ó le ṣe onídúró tí ó da'nto (Future Awards kàves in the Best Use Use of Advo)..
wikipedia
yo
Awon ise ti Makanjuola se wonyi ti fi opolopo anfaani kun ise eto omo ni orile-ede Naijiria nipasẹ LGBtiq, a si ka a kun eni ti o bere ise lori bi a ti le dẹkun ìfẹ̀tọ́-eni dun ni nipasẹ LGBTIQ.eto Eko Makanjuola keko gba imo nipa amojuto okoowo lati ile-eko imo nipa ijinle nipa okoowo ni ipinle Ogun, ni orile-ede Naijiria, (Ogun State Institute of Technology)..
wikipedia
yo
Ìmọ̀ nípa èè bí a ṣe lé ẹ ṣe àmójútó láti Yunifasiti Anglia Ruskin (strategic Project Management at Anglia Ruskin University) àti ẹ̀kọ́ ipilè nípa àmójútó iṣẹ́ àkànṣe lati Yunifasiti ti ìlú Ọba (Introduction Project Management Certificate at City University London). Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Pamela adìẹ́ jẹ́ ònkàtán, olùbá ọ̀pọ̀ èrò sọ̀rọ̀, àtò Ajijan-n-gbara fún ẹ̀tọ́ àwọn LGBT ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Pamela di ìlú mọ̀ọ́ká pẹ̀lú akitiyan rẹ̀ lórí ètò àwọ LGBTQ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Iṣẹ iwadi rẹ ni o da le LGBT Rights in Nigeria lóríṣiríṣi, lara iwe rẹ ti o ti ko ni under The Rainbow Ere ti o fi iriri rẹ han..
wikipedia
yo
Lára eré rẹ̀ ni ó ti ṣe àfihàn eré tí ó jó mọ́ bí obìnrin ṣe ń sóko obìnrin tí wọ́n pè ní ìfẹ́ ..
wikipedia
yo
Oun ni adari agba fun ajo ti kii se ti ijọba ti wọn pe ni equality hub.Ìgbé ayé rẹ Lóòtọ́ ni o ṣe igbeyawo ọkọ rẹ ọkunrin kan, amo o so ni gbangba wipe Olúfẹ̀ obirin bii tire ni oun ti awọn Gẹẹsi n pe ni LesBian, ikede yi ni o se ni ọdun 2011 nigba ti o ṣe ipade pẹlu awọn ẹbi rẹ..
wikipedia
yo
She Lajàgídíjàgan From CALABAR, Cross River State.Iṣẹ́ RePamela kẹkọ nípa ìmọ̀ òfin ni Ile-ẹkọ Webster University tí ó sì parí ẹ̀kọ́ Ọ̀mọ̀wé Masters degree rẹ̀ ní ilé-ẹ̀kọ́ University of Baltimore..
wikipedia
yo
O tun keko gboye akoko ni inu imo isakoso okowo Business Administration lati ile-eko University of Wisconsin-Superi..
wikipedia
yo
O tun lo keko nipa eto LGBT ti o sintibẹ̀ di obirin akokonti o je a Janfẹ̀tọ́ Awo LGBT ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo