cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Bákan náà ló tún jẹ́ akọ̀ròyìn fún ìwé ìròyìn "Vibe Magazine", ní èyí tí ó fi ń dá sí àwọn ìròyìn olóṣooṣù nípa orin àti àwọn ìròyìn tó jẹ mọ́ tàwọn ọ̀kọrin gbogbo..
wikipedia
yo
Wọ́n kàá ní oṣù karùn ún ọdún 2007 (May 2007) mọ́ àwọn obìnrin aláwọ̀ dúdú tí ó nípa jùlọ ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà (Ebony's '150 Most influential Blacks in America")..
wikipedia
yo
Lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí, òun ni ó dá Arise Entertainment 360 sileìgbésí aye rẹ̀ òun ni ìyàwó fún deen Asabo, tí wọ́n sì bí ọmọ ọkùnrin kan soso.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1975àwọn ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Lọlá Ògúnnáìkè jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tún jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà (American) tí ó jẹ́ amúlùúdùn àti oníròyìn ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Lọlá ní ọjọ́ kẹtàlá osù kẹsàn ọdún 1975 (September 13, 1975) ní ìlú New York City àmọ́ àwọn òbí rẹ̀ méjẽjì jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó gba oyè ẹ̀kọ́-kejì nínú iṣẹ́ ìròyìn ní ilé-ẹ̀kọ́ àgbà ti New York University , nígbà tí ó ti kọ́kọ́ gba oye ìmọ̀ àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Lítíréṣọ̀ Gẹ̀ẹ́sì (English Literature) nílé ẹ̀kọ́ àgbà University of Virginia.Ìgbòkè-gbodò iṣẹ́ rẹ̀ Ògúnnáì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí oníròyìn ní ọdún1999 nípa ṣíṣe ìròyìn amúlùúdùn àti àwọn àṣà míràn tó bá jẹ yọ..
wikipedia
yo
Lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí, òun ni ó dá Arise Entertainment 360 sileìgbésí aye rẹ̀ oun ni ìyàwó fún deen Asabo, ti wọ́n si bi ọmọ ọkùnrin kan soso.Àwọn ìtọ́ka síàwọn ìjápọ ìta àwọn Ọjọ́ìbí ní 1975àwọn ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
O fi igba kan dara po mo ẹgbẹ alatako APC ki o to pada si egbe PDP ni osu kefa odun 2014 ..
wikipedia
yo
Bi o tile je pe awon ebi re wa latiOsun, ilu Eko ni a ti bi, ni ojo-din-din-din-logun osu kewa odun 1960 fun OloyeVictor Babaremilekun Adetokunboh Fani-Kayode ati Oloye (Iyaafin) Adia Adunni Fani-Kayode..
wikipedia
yo
Oloye ni niIle-Ifeo wa lati iran Yoruba.Fani-Kayode ni oludamoran pataki pataki oro nipa ara ilu) fun Aare) fun Aare lati osu kejo odun 2003 titi di osu kefa odun 2006..
wikipedia
yo
A yan gegebi alamojuto oro to je mo asa ati Igba ni orile-ede Naijiria lati ojo keji-le-logun osu kefa si ojo keje osu kokanla odun 2006 ati gegebi alamoju fun oro to je mo irina oju ofurufu lati ojo keje osu Kọkànlá odun 2006 titi di ojo kokan-din-lọgbọn osu karun odun 2007.Ibẹrẹ igbe aye ati eko baba to bi baba baba re, alufa Èmánúẹ́lì Adedapo Kayode, je okan lara awon omo orile-ede Naijiria ti o koko lo ka'We ni ilu oba gb'oye ako'se mo'se lati ile eko Yunifasiti ti Durham, leyin eyi ti o di alufa ni ijo Áńgílíkan after which he became an Anglican priest..
wikipedia
yo
his grandfather, Victor Adedapo Kayode, studied law at Cambridge University and became a lawyer and a judge..
wikipedia
yo
His father Victor Baba113 Adé- Fani-Kayode, who was also at Cambridge was a prominent lawyer and political figure in Nigeria in the 1950s and Lefi..
wikipedia
yo
he was leader of the National Council of Nigeria and the Cameroons opposition in the Western House of Assembly from 1960 to 1963, The Hon..
wikipedia
yo
Minister of local government and TV Affairs and Deputy Premier of the Western Region of Nigeria from 1963 until 1966 and he successfully moved the motion for Nigeria's independence in 1958 in the Nigerian Parliament.References àwọn Ọjọ́ìbí ní 1960àwọn ènìyàn Alààyèàwọn agbẹjọ́ro ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Èyí ní ààtò àwọn fíìmù tí wọ́n ṣe ní orílẹ̀ èdè Ohund (list of films produced) àti ọdún tí wọ́n gbé wọn jáde.1992.. *
wikipedia
yo
Wọ́n bí Fọláṣadé Olayinka Baderinwa, tí wọ́n mọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ sí Ṣadé Baderinwa (/sa'dei: 'B:də-rìnwá: Shah-day Bah-dəd-in-wah), ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kerin, 1969..
wikipedia
yo
(born April 14, 1969) jẹ́ olùdarí ètò ní orí WABC ìkànì keje (Channel 7)..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó tún ṣe amúgbá-lẹ́gbẹ́ lórí ètò ọlọ́sẹ̀-ọ̀sẹ̀ pẹ̀lú Diana Williams tí ó ma ń wáyé ní dédé agogo márun ìrọ̀lẹ́ (Eyewitness News) àti ìròyìn alágo mọ́kànlá (11.pm News) kan pẹ̀lú Bill Ritter.Ṣadé dára pọ̀ mọ́ ilé ìṣe WABC ní ọdún 2003 lẹ́yìn tí ó ṣe nkan díẹ̀ ní ìlú abínibí rẹ̀ Baltimore, Maryland, ni bi tí ó ti darí ètò ìròyìn lórí WBAL-TV fún bí ọdún mẹ́ta..
wikipedia
yo
Ṣadé rọpo Roz Abrams, tí ó kúrò nílé iṣẹ́ yíi ní ọdún 2003 láti gbàṣẹ ní agogo márun sí mọ́kànlá alẹ́ (5 and 11 p.M.) ni WCBS-TV. Ní ọjọ́ kẹtàdín-logun oṣù keje, ọdún 2004 (July 23, 2004) nígbà tí ó ń múra láti jábọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ omíyalé tí ó ṣẹlẹ̀ ní Hackensack, New Jersey , ni olóko kan gbà tí ó sì sálọ (hit and run)..
wikipedia
yo
Sade padà Sidi iṣẹ́ rẹ̀ (Eyewitness News on December 13, 2004)..
wikipedia
yo
Ṣadé han ninu The View gege bi olugbalejo lori October 27, 2006..
wikipedia
yo
Bákan náà, ní Oṣù Karun (May, 2011), Bádérìnwá di amúgbá-legbe iroyin alaago mokanla (11 p.m..
wikipedia
yo
News) Pẹ̀lú Bill Ritter, tí òun náà sì ń rọ́pò Liz Cho, tí ó kúrò ní ipò adarí fún ìwé ìròyìn (new WABC 4 p.m newscast), èyí tí ó fẹsẹ̀ múlẹ̀ lẹ́yìn tí the Oprah Winfrey show kásẹ̀ kúrò nílẹ̀ tán tí Baderinwa sì tẹ̀ síwájú láti má bá ètò ìròyìn aláago márùn ún 5 p.m..
wikipedia
yo
Lo.baba re je Yoruba omo orile ede Naijria ti iya re si je omo ile German..
wikipedia
yo
Oruko re akoko ni "Folasade", to tumo si "Some who uses wealth as crown" ..
wikipedia
yo
Ó jáde ní ilé ẹ̀kọ́ àgbà ti University of Maryland College Park..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ìyá rẹ̀ ti jà kalẹ́ láti ọmọdé ti enika tí ó jẹ́ African American sì gbà tó amọ̀ òun àti bàbá rẹ̀ tó ń bẹ ní Nàìjíríà n sọ̀rọ̀ bákan.References àwọn Ọjọ́ìbí ní 1969àwọn ènìyàn Alààyè..
wikipedia
yo
Wọ́n bí Fọláṣadé Olayinka Baderinwa, tí wọ́n mọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀ sí Ṣadé Baderinwa (/sa'dei: 'B:də-rìnwá: Shah-day Bah-dəd-in-wah), ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹrin, 1969..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó tún ṣe amúgbá-lẹ́gbẹ́ lórí ètò olósẹ̀-ọ̀sẹ̀ pẹ̀lú Diana Williams tí ó ma ń wáyé ní dédé agogo márun ìrọ̀lẹ́ (Eyewitness News) àti ìròyìn alágo mọ́kànlá (11.pm News) kan pẹ̀lú Bill Ritter.Bàbá rẹ̀ jẹ́ Yorùbá ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ ilẹ̀ German..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ìyá rẹ̀ ti jà kalẹ́ láti ọmọdé tí ẹnìkan tí ó jẹ́ African American sì gbàá tó àmọ́ òun àti bàbá rẹ̀ tó ń bẹ ní Nàìjíríà ń sọ̀rọ̀ déédé.Ṣadé dára pọ̀ mọ́ ilé iṣẹ́ WABC ní ọdún 2003 lẹ́yìn tí ó ṣe díẹ̀ ní ìlú abínibí rẹ̀ Baltimore, Maryland, ní bí tí ó ti darí ètò ìròyìn lórí WBAL-TV fún bí ọdún mẹ́ta..
wikipedia
yo
Ṣadé rọpo Roz Abrams, tí ó kúrò nílé iṣẹ́ yìí ní ọdún 2003 láti gbàṣẹ ni agogo márùún sí mọ́kànlá alẹ́ (5 and 11 p.M.) Ní WCBS-TV. Ní ọjọ́ kẹtàdín-logun oṣù keje, ọdún 2004 (July 23, 2004) nígbà tí ó n múra láti jábọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ omíyalé tí ó ṣẹlẹ̀ ní Hackensack, New Jersey , ni olóko kan gbà tí ó sì sálọ (hit and run)..
wikipedia
yo
Ṣadé pada sídìí iṣẹ́ rẹ̀ (Eyewitness News on December 13, 2004)..
wikipedia
yo
Bákan náà, ní oṣù karùún (May, 2011), Bádérìnwá di amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ ìròyìn àlàgo mọ́kànlá (11 p.M..
wikipedia
yo
News) Pẹ̀lú Bill Ritter, tí òun náà sì ń rọ́pò Liz Cho, tí ó kúrò ní ipò adarí fún ìwé ìròyìn (new WABC 4 p.m newscast), èyí tí ó fẹsẹ̀ múlẹ̀ lẹ́yìn tí the Oprah Winfrey show kásẹ̀ kúrò nílẹ̀ tán tí Baderinwa sì tẹ̀ síwájú láti má bá ètò ìròyìn alágo márùn ún 5 p.m..
wikipedia
yo
lọ.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1969àwọn ẹ̀nìyàn alààyẹ̀..
wikipedia
yo
Wọ́n bí Gabriel Imomotimi Okara ní ojo kẹrìnlélọ́gbọ̀n Oṣù Kẹrin odun 1921 (born 24 April 1921)..
wikipedia
yo
O je akewi ati Olukọ̀tàn omo orile ede Naijria o je okan lara awon akewi igbalode (Modernist poet of Anglophone Africa) ile alawo dudu ti o n so Geesi..
wikipedia
yo
Ninu àwọn iwe itan aroso ati ewi re ni Okara ti ma n fi eko, esin, alo-onitan ati awon ami oniruuru ile alawo dudu han..
wikipedia
yo
Fun idi eyi, ni won se n pee ni "the Nigerian Negritukàkàkí". Gẹgẹ bi Ogande awon ise re Brenda Marie Osbey, se so, o ni "A le so wipe awon ise olokan-o-kan paapaa akoko ti Gabriel Okara koko ko ni ise litireso orile-ede gbe ewi-ede omi igbalode ti bere ti bere re ko re Imomotimi Gbaingbain Okara, je omo oloye ile ijo kan, won bi ni ilu bo ilu Niger Delta Delta ni odun 1921 ni odun 1921..
wikipedia
yo
O keko nile eko ijoba ti government College Uahia, ti o si tun lo si ile eko agba ti later Yaba Higher College..
wikipedia
yo
Lasiko ogun agbaye elekeji (World War II), o gbiyanju lati dara po mo omo ogun oke ti ile Britiko iyen British Royal Air sugbon ko pari eko wiwa oko ofurufu, amo o ba ile ise okunrin ti ti British over Airway Corporation ti won pada yi si (British si odun York).Ní odun 1945, Okara gege gege bi atewe fun ile ise ise Folawiyo ile Naijiria..
wikipedia
yo
O sise ni ile ise yii titi di igba ti oun naa fi bere si ni kowe jade..
wikipedia
yo
Ó kọ́kọ́ idàta ewì kan láti èdè Ijaw sí èdè Gẹ̀ẹ́sì, tí ó sì kọ ìwé fún ilé iṣẹ́ ìròyìn Asọ̀rọ̀-mágbèsì Ìjọba ..
wikipedia
yo
Lára àwọn ewì rẹ̀ ni wọ́n tẹ̀ jáde nínú ìwé ìròyìn ọlọ́sẹ̀-ọ̀sẹ̀ ti Black Orpheus, ní 1960 ó ti di ìlú mọ̀ọ́ká lórí àgbékalẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ àwọn ewì rẹ̀ ni wọ́n ti ṣe ògbufọ̀ rẹ̀ sí oríṣiríṣi èdè..
wikipedia
yo
Ohun ti o je Okara lokan ju ni ipenija ti asa ati ise ile Adulawo n koju latari olaju awon oyinbo Western Culture, ni eyi ti ewi re "Once Upon a Time" so nipa rẹ.O ṣafihan akori naa ninu itan aroso re ti, The Voice (1964). ti olú ti olú itan Òkolo, feran asa awon le Geesi ju awon ami ibile re lo lati ewi lo ewi re ati itan re Okara tun ti ko ere onise ti won ti ka sẹ ti ka awon ara awon ara awon egbe eye opo awon aroko ti ko tii di tite jade lo tite lo omo naa se April 2017.Ni April 2017, won se litireso ti won pe ni (Gabriel Okara Literary Festival) ni ogba Eko ile eko University ofPort Harcourt lati fi Seye fun ojogbon. ojogbon ja lati
wikipedia
yo
Magka gbe iwe kan jade ti o pe ni "Gabriel Osting" May 2017. ti o fi ṣalaye pe pe ni won ko fi si ipo ti ipo ti o san ki o wa laarin awon onkowe Adulawo" ..
wikipedia
yo
Solomon Adeboye Babalola ni won bi ni ojo ketadinlogun osu ope, odun 1926, o ku ni ojo keedogun osu kejila, odun 2008 (December 17, 1926- December 15, 2008), ni ilu Ipetumodu, ni Ipinle Osun, ni orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ olùkọ́, akéwì àti onímọ̀.Ìgbésí ayé rẹ̀ Ọ̀jọ̀gbọ́n Solomon Adeboye Babalola jẹ́ ọmọ ìdílé Babalola ti ilé - Àjọ..
wikipedia
yo
Baba rẹ̀ Joseph Ọláwuni Omowumi Babalola (Àjàlá) jẹ́ gbẹ́nà-gbẹ́nà, ní sẹ́nuturi ogun ó tún ilé àwọn èèyàn ti ìjì wó kọ́, wọ́n mọ rírì ifọmọnìyànṣe àti àánú rẹ̀ yìí, wọ́n sì fún ìdílé wọn ní orúkọ “alátúnṣe ti Ipetumodu”
wikipedia
yo
Wọ́n ṣe ìrìbọmi fún sinu ìjọ Ṣọ́ọ̀ṣì Kírísítì ti Ṣọ́ọ̀ṣì Àwọn Ajíhinwhere Christ Church of the Church Missionary – C..
wikipedia
yo
Wọ́n fi ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ tó jinlẹ̀ tó ní kékeré, ó lọ sí ilẹ̀ilẹ̀ Alawíwà Kírísítì (Christ Primary School), wásíimi, Ipetumodu..
wikipedia
yo
Akọrin ṣọ́ọ̀ṣì ni, tí ó sì má ń kọrin nínú balùwẹ̀ nígbà ayé rẹ̀..
wikipedia
yo
Babalọlá gba Kírísítì gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run àti Olùgbàlà rẹ̀ nígbà tí ó wà ní kọ́lẹ́jì Igbobi, tí bíṣpù rt..
wikipedia
yo
Rev Gordon ti ilu Eko si se ijẹrisi.Babalola lo si ile-eko Achimota College ni orile ede Ghana..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè tán ní ọdún 1946, ó ṣiṣẹ́ olùkọ́ ní Igbobi College..
wikipedia
yo
Ni ọdun1948, o gba ẹbun Eko ọfẹ elekeji lati ko Eko nílé Eko Queens' College, Cambridge, nibi ti o tun ti gba oye oye Imo Eru ni ọdun 1952..
wikipedia
yo
O tun pada si Igbobi College lati te siwaju lori ise ikoni re ti o si ri agbega ti o fi di oluko agba ti o je Adulawo ile-eko naa , pelu bi o se je wipe oun ni oluko ti ojo ori re kere julo julo awon oluko ile eko naa..
wikipedia
yo
Wọ́n fún ní ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ Ọ̀mọ̀wé (Dodo scholarship) nínú LÍTÍRÉṢỌ̀ èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1962, wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ nílẹ ẹ̀kọ́ Institute of African Studies ti Obafemi Awolowo University..
wikipedia
yo
O tun jẹ anfani eto imo Eko ọfẹ lọ sile eko University of London lati gba oye imo omowe..
wikipedia
yo
Ni ọdun 1963 , o di ojogbon ninu imo ede ile Adulawo (professor of African languages) ni ile eko University of Lagos..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1966, ó tẹ ìwé The content and form of Yoruba Ìjálá,ti ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé Oxford University Press gbé jáde..
wikipedia
yo
IṢẸ́ NÁÀ SỌ NÍPA alo ONÍTÀN Yoruba,ÀWỌN EWÌ lóríṣiríṣi àti àkójọpọ̀ àwọn ewì ìjálá ọdẹ (hunter's Songs), tí wọ́n sof€78ó re sí èdè Gẹ̀ẹ́sì..
wikipedia
yo
Ìwé náà gba àmì ẹ̀yẹ ti Amary Talt Prize fún iṣẹ́ tó peregedé jùlọ lọ́dún náà fún LÍTÍRÉṢỌ̀ àwọn ènìyàn apá ìwọ̀-oorun ilẹ̀ Adu..
wikipedia
yo
Ìwé náà tún ṣílẹ̀kùn fún ìwádí nípa èdè Ilẹ̀ Adúláwọ̀ ní gbogbo AbGaye, lábẹ́ àkóso Babalola ní University of Lagos..
wikipedia
yo
Lámúí iṣẹ́ àpilẹ̀kọ Babalọlá kó ipa ribiribi fún Ísọ̀lọ́jọ̀ Àwọn Lítíréṣọ̀ alohùn..
wikipedia
yo
Babalola wo Kaa ile lo ni ojo keedogun osu ope, odun 2008awon itọkasi People from Osun Statatẹ́júkhos AcadémicsNigerian male pòtsYorùbá poetSalu of the University of LondonYorùbá AcadémicsYorùbá-language writerSalu of Achimota Schoolọbami Awólọ́wọ̀ University FacultyUniversity of Lagos Fcult ni of Queens' College, CambridgeYorùbá-language pòts Ducators educators eduloNigerian Folklo-teachers-teachers-century Nigerian wọ́dets Nigerian China Ọjọ́ìbí ni 1926 ni 2008 ni 2008..
wikipedia
yo
Femi Falana San (Senior Advocha of Nigeria) jẹ́ agbẹjọ́rò àti ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹdọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá, ọdún 1958.(30 December, 1958)..
wikipedia
yo
O dije dupo Gomina ni ipinle Ekiti ni odun 2007 sugbon o padanu ibo naa labẹ ẹgbẹ oṣelu NCP (National Conon Party) ti o ti fìgbà kan je Alaga ẹgbẹ naa jákè-jádò Naijiria ni ọdun 2011..Bákan náà, oun ni baba fun ọ̀kọrin, Adérì KOonpo ati oṣere ori itage ti orukọ rẹ n je Falz..
wikipedia
yo
Femi je oko fun arabinrin Funmi Falana ti oun naa tun je ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn ni orile ede Naijiria.Awon itọka si awon Ọjọ́ìbí ni 1958awon eniyan Alààyèawon agbejoro ara Nàìese Naijiria ara Nàìese agbejoro agba Naijiria..
wikipedia
yo
Ijó AngNoumair ìjọ AngNoumair jẹ́ ìjọ tí ó tóbi ṣe ìkẹrin nínú Àgbáríjọ pọ̀ àwọn ọmọ lẹ́yìn Kristi káàkiri àgbáyé pẹ̀lú ọmọ ìjọ tí ó tó mílíọ̀nù márùn-lé-lọ́gọ́rin ènìyàn...
wikipedia
yo
Ràsákì àkànní Okoya ni wọ́n bí ní Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọjọ́ kejila oṣù kìíní, ọdún 1940 (12 January 1940). Ó jẹ́ gbajúgbajà ìlúmọ̀ọ́ká oníṣòwò, olówó tabua tí ó ní ilé iṣẹ́ púpọ̀..
wikipedia
yo
AÁYAN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ rẹ Razaq Okoya kẹ́kọ̀ọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ re nile eko alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Ansar-un-deen, Oke Popo, ní Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Oun ni alase ati oludasile ile-ise Eleganza Group, ti o n ta oja jakejado ile Adulawo (Western Africa).ibẹrẹ igbesi aye rẹ Oloye Razak Okoya je omo Yoruba lati ariwa iwo Oorun (South-western) Naijiria..
wikipedia
yo
Wọ́n bí ní ìoodle ọ̀gbẹ́ni Tiamiyu Ayinde Okoya ní ìlú Èkó ..
wikipedia
yo
Ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú baba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aránsọ tí baba rẹ̀ jẹ́, tí wọ́n sì tún n ta àwọn ohun èlò ìránṣọ pẹ̀lú . ìmọ̀ tí ó ní lọ fún ní ìgboyà láti dá dúró fúnra rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá..
wikipedia
yo
O tu owo jo ti o fi pe Ogun poun (20 PRI), ti iya re naa si Raan lowo pelu aadọta poun (50 PRI), lati fi bere owo tita ati rira lati ile Japan.Iṣẹ OKÒWÒ re ile ise waye kia waye kia ninu n si n ati mo kaakiri lati mo se n pese ti o pese ni o se ni o se ni orile ede Naijiria bi akoko Naijiria bi tàwọn ti oruko ti oruko re n je Okoya ku osu feran ki o feran ki o bere awon ohun oso ona waye pamo ti Razak si ma si ma n se bi won to won to won to won to si ilu tòsí lati o pese lati bu ti o ko si n ilu awon omo awon mo si awon bere ori pelu won pese ti o ni owo ko ni o se ni o se ni awon ni awon ni ori ede Naijiria ni awon nibi naa se n pese lati o feran ki bere ti o fi ni ilu ko ni o feran ki o feran ki o bere ori ori ori ori ori naa to lati ori ko ni o fi ori ori ni o se ni o tun ni orile ori naa ni akoko naa ni ilu to ori lati ori lati fi bere ori lati o se ni o feran ki o ma ori ori ori ni orile ede re si ori naa se ori ori ori ori se ori se*_
wikipedia
yo
O mọ̀ wípé iye owó àwọn oṣó ara wọ̀nyí kò kéré, àtipé òun lè má ṣe wọn nílẹ̀ Nàìjíríà ìgbà tí owó ohun ìpèsè rẹ̀ kọ́ wọn ní ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Okoya tun rin iri ajo lo si ile okere lati ra ero ti o le pese awon ohun oso ara naa..
wikipedia
yo
Nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní pèsè rẹ̀ ní ọ̀nà ara tí ó sì ń táa ní owó pọ́ọ́kú, àwọn ènìyàn bòó apá rẹ̀ kò sì fẹ́ ká bí àwọn ènìyàn ṣe ń béèrè fún ọjà rẹ̀ mọ́..
wikipedia
yo
ó bẹ̀rẹ̀ kíkọ́ àwọn bàtà gidi lọ́pọ̀ yanturu, láì mọye ìgbà ni àwọn ọjà rẹ kìí tètè dé pẹ̀lú bí o ṣe ń tètè san owó asán sílẹ̀..
wikipedia
yo
O ṣẹ̀rín ajo lo ile Italy lati ri awon ti won n se bata naa, iyalẹnu lo je fun wipe won ti fi owo oja re san gbese tiwon..
wikipedia
yo
Bayi ni ó ṣe pinu lati dá ilẹ̀ iṣẹ́ bàtà tirẹ̀ náà sílẹ̀..
wikipedia
yo
O ra awon ero to lagbara lati sise naa ti o si gba awon akose-mose lati ko awon osise re ni ile Naijiria bi won se n pese bata.loni, labe akoso re,ile ise Eleganza ti n pese orisirisi ohun elo ile..
wikipedia
yo
Ile ise akojopo Eleganza je okan lara awon ile ise to laami laka jake jado ile Naijiria , ti o si tun ni o kere tan mefa kaakiri awon orile ede to sunmo ile Naijiria..
wikipedia
yo
ó ti gba àmì ẹ̀yẹ ìdáni-lọ́la fún ìdí àṣeyọrí okòwò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùdásílẹ̀ iṣẹ́ ara-ẹni àsìkò tiwa (Business Entrepreneur of Our Time) láti owó ìwé ìròyìn Newspapers Newspapers.Àwọn ọ̀rọ̀ ọ̀jọ̀gbọ́n rẹ̀ ""nílé ìwé, mo ní ànfàní láti sesa iṣẹ́ òkòwò nígbà tí mo rí àwọn olùkọ́ mi nínú àwọn aṣọ tó ti gbó; tí mo sì rí oníṣẹ́ okòwò tó n wọ aṣọ pàtàkì láàrin Ọjà Ddaramu tí ó jẹ́ ojú Ọjà Oníṣègùn nígbà náà.”“Mo ma ń ṣọ́ra mi..
wikipedia
yo
Ohun ti a ma n wo ni pípèsè ohun ti àwọn ènìyàn lè rà lówó pọ́ọ́kú.Eyi jẹ́ ọ̀kan lára àṣírí mi." ""Ohun tí ó jẹ́ ìwúrí fún mi ni wípé mo fẹ́ jẹ́ olọ́lá, mo sì mọ̀ wípé mo ti ṣiṣẹ́ gidigidi láti dé ipò náà.”“Mi ò ní èrò kérò sí kíkẹ́kọ̀ọ́..
wikipedia
yo
Sugbon nigba miran, iwe kika ma n se awon eniyan ni akin ti kii se ootọ..
wikipedia
yo
O ma n je ki won Fọkàn bale lori iwe eri won laiṣakitiyan lati ni Ola."Awon omo re Oloye Razak Okoya bi omo maruun..
wikipedia
yo
Sugbon, eyi ti o wa loju ọpọ́n lowo ni iya Afin Folasade Okoya ti Oloye Razak Okoya so wipe o ma sise kara kara..
wikipedia
yo
Oun naa lo bi awon (Olamide, Oyinlola, Subomi and Wahab) fun..
wikipedia
yo
Sade paa paa ti gba opo ami eye idani-lola gege bi eni to mo araamu julo ti awon funfun si n kose re.Awon itọka si awon onisowo ara Naijiria..
wikipedia
yo
Lasiko 2014 niNaijiria, HIVlaarin awon odo to ti sele to ti to omo omo odun meedogun si South 3.17 ni owoNaijiria.17.17 ni o gbe ipo keji ninu awon ti o n semi pelu arun HIV.arun HIV.arun HIV di ajakale ti o si po ju ara won lo ni agbegbe si agbegbe..
wikipedia
yo
Awujo awa ara wa (Civil society)ko fese mule lasiko isejoba awon ologun ni orile edeNaijiria..
wikipedia
yo
Onka ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà nígbà náà nira lati mọ paa paa nígbà akitiyan àti se ìjọba àwa arawa lati le fese ise ijoba ilẹ̀ Nàìjíríà mule (Nigerian government)ko ipalara ba ise deede nípa eto eto ìlera (Health) kaakiri awon agbegbe orile ede naa.Isakoso awon alakale eto lẹ́sẹẹsẹ lati ori ijoba apapo, ijoba ipinle si ipinle ati ijoba ibile mu isoro wa lopolopo..
wikipedia
yo
àwọn iléeṣẹ́ ètò ìléra tí ó jẹ́ ti aládáni ni kò rí àmójútó dára dára, pàápàá jùlọ ni kò ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú iléeṣẹ́ ètò ìléra ti ìjọba níbi ti Èkó nípa àrùn HIV àti ìmójútó àwọn ènìyàn ti kéré jọjọ..
wikipedia
yo
Ìtọ́jú àti ìrànlọ́wọ́ kò tó ǹkan láti ọwọ́ àwọn dókítà àti nọ́ọ̀sì, nítorí iṣẹ́ ti pọ̀ jù wọ́n lọ.Àti wípé wọn kò ní ìmọ̀ àti ẹ̀kọ́ tó péye láti pèsè ètò ìlera tó yanrantí fún àwọn aláìsàn náà.Ẹ tún lè wọ AIDS Manase Health Care in Nigeria HIV/AIDS in AFRIABÀWỌN Ìtọ́ka Sí..
wikipedia
yo
Wọ́n bí Olóyè Wahab (AbdulWahab) Iyanda Folawiyo ní June 16, 1928 , Ó ku ní ​ June, 2008..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríàtí ó sì jẹ́ olùrànl-lówó fún àwọn ènìyàn.Ní ọdún1957, O 1957, ó da ilé iṣẹ́ ihò Folawiyo & Sons kalẹ̀, èyí tí ìpìlẹ̀ jé ìpìlẹ̀ fún àwọn ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ilé isé isé rèé tó kú. Wọn bí kò tún ewé osù Èkó sí ìdílé pa tí ó jé oníṣòwò pẹ̀lú oníṣòwò pẹ̀lú oníṣòwo pẹ̀lú ìjọba amúnisìn (British igbọnwọ ènìyàn yé Né)..
wikipedia
yo