cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Johnson ati Cynthia Johnson nílùú Houston, [[Texas]]..
wikipedia
yo
Ní déédé ọmọ ọdún mẹ́rìnlá (age 14), Johnson lọ sí [[Oakland]], ìpínlẹ̀ [[California]] ó kàwé ní ilé-ìwé gíga ti Oakland Technical High School ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní ọdún 1984..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó kàwé-gboyè tán, ó forúkọ sílẹ̀ láti dara pọ̀ mọ́ ọmọ ogun ilẹ̀ Amẹ́ríkà U.S..
wikipedia
yo
Tí ó sì sin ilé baba rẹ̀ fún ọdún mẹ́fà gbáko.Ìtàn iṣẹ́ agbófinró rẹ̀ Johnson sin ilé baba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọlọ́pàá ọmọ ogun military policeman nínú ọmọ-ogun U.S..
wikipedia
yo
Àti gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ma ń ṣàtúnṣe sí ìwà ọ̀daràn nílé iṣẹ́ ọlọ́pàá Texas Department of Criminal Justice ṣáájú kí ó tó dara pọ̀ mọ́ ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá Houston Police Department ní 1994..
wikipedia
yo
Wọ́n fún ní àmì ẹ̀yẹ ẹni tí ó ma ń gba ẹ̀mí ará ìlú là jùlọ láti ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá Houston Police Department àti àmì ẹ̀yẹ akínkanjú ní Texas bákan náà fún iṣẹ́ tí ó ṣe ní Southeast Gang Task Force..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó sin Southeast Gang Task Force tán, wọ́n gbe lọ sí traffic Division, ní ibi tí ó ti fẹ́ràn iṣẹ́ tí ó tún ṣe síi gidi-gìdì..
wikipedia
yo
Ìyàwó rẹ̀, Joslyn Johnson náà tún jẹ́ Sergeant ní ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá Houston.Iṣẹ́ tí ṣe kẹ́yìn kó tó kú ní ọjọ́ kọkàn-lọ̀ oṣù kẹsan, ọdún 2006 (September 21, 2006,) Johnson gan ni ọkọ ti ó ń sáré àsápajúdé kan ní ìwọ̀n 50 òdòdópé sí 30 òdòdópé ní òpópónà Randolph nitosi Braniff, tí ó ún Súmọ́ William p..
wikipedia
yo
Oko tí8 ó sáré asa-Olùgbàlà yìí jẹ́ ọkọ̀ ọlọ́pọ́n-ìrúbọ (Ford Picbúọ̀gá Truck) ni èyí tí ó jẹ́ pé Juan Leonardo Quintero lo waa..
wikipedia
yo
Johnson da oko naa duro, ti o si beere fun iwe-awako Quintero ni eyi ti..
wikipedia
yo
Jhonson ba kuku mu ti o si fi mamu-gaari si lowo, o tii sinu oko agbowo re, o ti lekun mo..
wikipedia
yo
Ní ti Jhonson tí n ṣe èyí lọ́wọ́ ní Quintero tí kò pala yí owó rẹ̀ padà síwájú ìtíṣe ti mamu-gaari owó rẹ̀, tí ó sì mú ìbọn ìléwọ́ kan 9mm Caliber Handgun tí ó so mọ́ okùn idi rẹ̀ tí ó sì yiín fún ọlọ́pàá Johnson Johnson, amo kí Jhonson tó kú, ó gbìyànjú láti tẹ et ẹ̀rọ ipe 72- tí ó wà níbi ọkọ rẹ̀, ní èyí tí ó ṣòfófó fún ilé-iṣẹ́ ọlọ́ọlọ́pàá wípé lẹ́hìn kan wà nínú idaan lọ́wọ́ lọ́wọ́..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí Quintero yinbọn lu Johnson tan, ó tún yìnbọn ti oko ẹ̀ṣọ́ ojú pópó tó wà nítòsí ibẹ̀ ṣùgbọ́n ó tàsé..
wikipedia
yo
Nígbà tí àwọn òlọ́lọ̣́ tó kù láẹ̀, wọ́n bá Quintero leni tí ó sì ń sẹ́yìn ọkọ̀ tí j-ìgbéraga fi sí tou ti “Ahoro-gaari owó rẹ̀ pẹ̀lú ìbò t mú ṣù..
wikipedia
yo
Won si fi Quintero si ahamo rtin igba naa.Ìsìnkú ati iseye eni rere ojo ketadinogun osu kesan odun 2006 (September 27, 2006) ni won sin Johnson..
wikipedia
yo
O le ni egberun merin eniyan ti o wa sibi ayeye isinku oloogbe naa, yato si laami-laaka ninu ise olopaa ni ipinle naa idawo jo po ti o le ni $87,000 ni won da jo fun iese olopaa olopaa ologbee naa..
wikipedia
yo
Ti egbe (organization for family members of fallen firefighters and police officers) naa si tun Seye tiwon naa fun...
wikipedia
yo
Ọlọ́lá-Jùlọ ti Ipinle Texas iye Rick Perry naa da Jhonson lola pẹlu ami eye ti 'Star of Texas Award', eyi ti won ma n fun akoni agbofinro tọba ku sẹ́nu ise re, kódà awon omo ile igbimo asofin agba ti Ipinle Texas..
wikipedia
yo
The Texas Senate náà tún fun ní àmì ẹ̀yẹ ìdáni-lola.ìpéjọ ọ̀pọ̀ ìyàwó Johnson tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Joslyn pé ẹjọ́ Meri ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lẹ́yìn ikú ọkọ rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2008, ó pe ilese ọlọ́pàá tí ọkọ rẹ̀ ṣiṣẹ́ kẹ́yìn lẹ́jọ́ wípé ìyẹn Houston Police Department fún 'IKÚ aito' Àtàrí wípé ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá náà pé wọ́n kò gba ọlọ́pàá méjì láyè àti ṣíṣe pọ̀..
wikipedia
yo
Èkejì ni pípe aájò Houston lẹ́jọ́ lórí ‘ ìkùnà lórí fura ilésse àwọn ọlọ́pàá ojú pópó létí orúkọ àwọn arúfin ètò ìrìn-àjò tọ́wọ́ àwọn agbófinró tó ń rí sí ètò ìwọléwọ̀de arìnrìn-àjò ní ẹ̀pí náà’ tí ó sì bu ẹnu àtẹ́ lù wípé kò bófin mu..
wikipedia
yo
Ni 2010, wọ́n da ẹjọ́ yìí nù ní ilé ẹjọ́ àpapọ̀ kan tí ó ń jẹ́ Federal District Court tí wọ́n sin sọ wípé ẹjọ́ náà ti fara pẹ́ ẹjọ́ àkọ́kọ́ jù..
wikipedia
yo
Court of Appeals for the Fifth Circuit Sayi padà lórí èrò wọn pẹ̀lú ìwádí wípé " Ẹ̀sùn Joslyn Jhonson tako ọ̀pọ̀ nínú òfin tí wọ́n ìyẹn 'HPD' ní èyí tó ṣófa ikú ọ̀gbẹ́ni Rodney Jhonson."ọ̀daràn Juan Leonardo Quintero, tí ó jẹ́ ọmọ márùndínlógójì (35), ni ó jẹ́ arìnrìn-àjò lọ́nà tí kò bófin mu, tí ó sì tún ní àkọsílẹ̀ wípé ó ní àrùn ọpọlọ àtàrí ìṣubú rẹ̀ Látìgbà ewé rẹ̀..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1994, lọ́nà àìkánkán nípa dá Matamoros kọjá tí ó ṣí Houston. Wọ́n tún mú ní 1995 fún ìwà ọ̀mùtí para, bákan náà ni wọ́n tún m fún wíwá ọkọ pẹ̀lú ìwé ìdánimọ̀ tí wọ́n fura sí ní 1996..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1998, ó bẹ̀bẹ̀ fún ìdáríjì lórí ìwà àìtọ́ tó hù sí ọmọdé-bìnrin ọmọ ọdún Mejía (12)kan pẹ̀lú kí wọ́n bá pọ́ùn fọwọ́ eo ejò náà sẹ́yìn..
wikipedia
yo
Ní April 1999, wọ́n tìí mọ́lẹ̀ fún rírúfin ìrìnà, tí wọ́n sì dá padà sí Mexico ní oṣù tó tẹ̀ lé..
wikipedia
yo
Ni opin odun 1999, eni ti o ni okowo landscaping business ti o gba Quintero sise ni Houston ya ni owo pe ki o fi ya oko ka ti won n pe ni coyote pe ki o fi ko fi se fàyàwọ́ koja ni ibodè .Nigban ti Quintero eto Gbemi Johnson, kia ni won ti mu ti wo si fi si ahamo awo olopaa . O bebe pe oun ko moomo paa lati wipe ori ou ko pe rara..
wikipedia
yo
Adájọ́ tí ó gbọ́ ẹjọ́ náà kò tẹ́tí gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀, ó sì dájọ́ ẹ̀wọ̀n gbére fún ní ọdún 2008..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀, ó btún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tí ọwọ́ tẹ̀ lásìkò tí wọ́n gbìyànjú láti sá jáde ní ọgbà ẹ̀wọ̀n Allan B..
wikipedia
yo
PoLunda unit, ogba ẹ̀wọ̀n tí ó wà ní Livington, Texas, ní ọdún 2010.Ṣiṣẹ́ ìdájọ́ agbódegbà ọ̀daràn náà ní ọdún 2009, Robert Lane Camp, ẹni tí ó ní ilese landscaping tí ó gba Quintero ṣíṣẹ́, tí ó sì ya nílé gbé jẹ́wọ́ pé lóòtọ́ ni òun jẹ̀bi ẹ̀sùn tí ìjọba fi kan òun pé òun gba àlejò àìtọ́ tó wọ̀ lọ́nà àìtọ́ sílẹ̀ ti oú sí Raan lowlo láti hùwà ọ̀daràn ṣùgbọ́n kì í dákun-dabo kí wọ́n fowó wọnú lílé oun ní ilé-ẹjọ́ ẹjọ́ U.S..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2010 ni wọ́n dá Camp lẹ́jọ́ ẹ̀wọ̀n osù mẹ́ta péré nínu ie ara rẹ̀( home confinement), tí wọ́n sì tún fi sí abẹ́ ìsọ̀ awo lọ́lọ́ fu odidi óó marún..
wikipedia
yo
Eléyìí yóò jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ìjìyà àti ìkìlọ̀ fún ẹnikẹ́ni tí ó bá tún gba àlejò tó wọ̀lú lọ́nà àìtọ́ gẹ́gẹ́ bí òun ti ú.S..
wikipedia
yo
Bimbo Akintola (tí wọ́n bí ní ọjọ́ karùn-ún, Oṣù Karùn-ún Ọdún 1970) jẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbé ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Akintola ní ọjọ́ karùn ún Oṣù karùn-ún Ọdún 1970 bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ẹdó..
wikipedia
yo
O lo si ile-iwe alakọbẹrẹ ti àwọn Ìjọ Àgùdà ti o wa ni ni agbegbe Maryland ni ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí, ó tẹ̀síwájú lọ sí ilé ẹ̀kọ́ girama ti àwọn ológun tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
O k'eko gboye imo nipa ere ori itage lati ile eko giga Yunifasiti ti Ibadan.Iṣẹ ise akoko ti o gbe jade ni eyi ti o se ninu fiimu Owo Blow ni odun 1995, eleyi ti oun atiFemi Adebayo jo se ati eyi ti o tun se leyin re ti a n pe ni Out of Boundsni odun 1997ti o se pelu Richard Mofe Damijo..
wikipedia
yo
Àwọn òǹwòran fíìmù sọ wípé òun ni ó mọ eré ìtàgé ṣe jù ní ọdún 2013 nígbà tí wọ́n wo ipa tí ó kó nínu fíìmù ní ọdún 2013 nínu ètò tí a ti ń mọ èyítí àwọn eléré orí ìtàgé ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Àwọn àṣàyàn iṣẹ́ ọwọ́ Blow (ọdún 1995) Out of Bounds (Ọdún 1997) The Gardner (ọdún 1998) Dangerous Twins (ọdún 2004) Beyond the Verdict (ọdún 2007) Smoke and Mirrors (ọdún 2008) Hoodrush (ọdún 2012) Aroko (ọdún 2013) Heaven's Hell (ọdún 2015) 93 Days (ọdún 2016)Àwọn Itọ́ka sí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1970àwọn ènìyàn Alààyèàwọn òṣèré ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Dorota RaBCaṣebika (ọjọ́ìbí 15 February, 1984) jẹ́ òṣèré ara orílẹ̀-èdè Poland.Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1984àwọn Ara Póilandi..
wikipedia
yo
Tegui calderon Rosario (ojoibi February 1, 1972), jẹ́ Puerto Rican Ilẹ̀ọba àti Broẹtọn singer.Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1972àwọn olórin Rap ara Puerto Rico..
wikipedia
yo
Alan Alejandro Maldonado TaMez (ọjọ́ September 24, 1984), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ dharius, jẹ́ Mexican Ilẹ̀ọba..
wikipedia
yo
Dharius gbajúmọ̀ Be Híso láti Gangsta Rapàwọn Ọjọ́ìbí ní 1984àwọn Olórin Rap ará Mefarakàn..
wikipedia
yo
Ọ̀jọ̀gbọ́n Akinwunmi Isola ni a bi ni ojo kẹrinlelogun osukejila, odun 1939 ti o si tẹ̀rí ni ojoda ni ojo keta osu keji, odun 2018.(24 December 1939–17 17 February 2018) ni o je omo orile edeNaijiria, o si tun je Oluosu-itage, osere-ori, olugba-itage,sa onimo esin ijinle..
wikipedia
yo
Ó di ìlú-mọ̀ọ́ká jákè jádò àgbáyé fún ìmọ̀ ìṣòwò kọ̀wé rẹ̀ àti bí ó ṣe ń gbé àṣà pàá pàá Yorùbá lárugẹ.Ìtàn ayé rẹ̀ àti àwọn iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí ìṣọ̀lá ní ìgboro ìlú Ìbàdàn ní ọdún 1939, ó sì lọ sí ilé ìwé alákọ̀ọ́kọ́-bèrè lábodè Methodist School àti ilé ìwé gíga ti Wesley College. Bákan náà ló tún lọ sí ilé ìwé ẹ̀kọ́ àgbà ti Ìbàdàn (University of Ìbàdàn), níbi tí ó ti gba oyè B.A..
wikipedia
yo
Bákan náà ló tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú Lítíréṣọ̀ Èdè Yorùbá ní ilé ẹ̀kọ́ àgbà ti ìlú Èkó (University of Lagos) ní ọdún 1978 ṣáájú kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ni ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti (Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University) ní Ilé-Ifẹ̀.Wọ́n fún Ọ̀jọ̀gbọ́n Akínwùmí Ìṣọ̀lá ní oyè ọ̀jọ̀gbọ́n ní Ilé-Ifẹ̀ Bákan náà ní ọdún 1991 gẹ́gẹ́ bí àmì ìdánimọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ kan eré oníṣe onítàn kan tí ó kọ́kọ́ kọ́ ní ọdún 1961 sí 1962 ìyẹn Ẹfúnṣetán Aníwúrà, nígbà tí ó wà ní akẹ́kọ̀ọ́ nílé ẹ̀kọ́ àgbà ti Ìbàdàn..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn èyí ni ó kọ ìwé eré oníṣe ó lekú ní ọdún 1986, òun ni ó tún kọ orin ìwúrí ilé-ẹ̀kọ́ náà tí wọ́n ń kọ nílé ẹ̀kọ́ náà títí dòní ní Fásitì Ìbàdàn.Lẹ́yìn àwọn ìwé ìtàn àròsọ òkè wọ̀nyí, ó tún tẹ̀ síwájú láti kó onírúurú àwọn ìwé eré onítàn, eré oníṣe, ìtàn ọlọ́rọ̀ geere àti oríṣiríṣi àwọn ìtàn akọni ìgbà ìwáṣẹ̀..
wikipedia
yo
Bakan naa lọ́tùn Pékà de ilé iṣẹ́ ìwé ìròyìn tí ó sì tún ní ilé iṣẹ́ tí ó n gbé onírúurú àwọn ìtàn eré oníṣe tí ó ti kó jáde sí sinimá àgbéléwò..
wikipedia
yo
Ẹ̀wẹ̀, Ìṣọ̀lá kò ṣàì kọ́ ọlọ́kan ò jọ̀kan ìtàn ní èdè Gẹ̀ẹ́sì tí ó sì tún idàye ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ àpilẹ̀kọ ní èdè Gẹ̀ẹ́sì( English) sí èdè abínibí rẹ̀ tii ṣe èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Bákan náà ló tún jẹ́ Olùkọ́ Alábẹ̀wò sí ilé ìwé Èkó àgbà ti ilẹ̀ Jógia (University of Georgia).Àwọn ẹbí rẹ̀ Akinwunmi ìṣọ̀lá fẹ́ ìyàwó tí ó sì bímọ mẹrin.Ìpajẹun rẹ̀ Akinwunmi ìṣọ̀lá kú nínú ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kejì ọdún 2018, tí wọ́n sì sin sí Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ọmọ ọdún méjìdínlọ́gọrin (78) ni Ìṣọ̀lá ṣáájú ikú rẹ̀.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn Olùkọ̀wé ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Wọ́n bí Peter Fátómilọ́lá' ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kínní ọdún 1946..
wikipedia
yo
O je omo bibi orile-edeNaijiria, o si je osere ori itage, Olukọ̀tàn, akewi ati ògúná gbongbo nibi ka ko ere-onise (playwright.)ibẹrẹ igbesi aye rẹ won bi Peter Fátómilola ni ojo kerindinlogun osu kinni odun 1946 si ijoba ibile ifisan Ekiti..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ Olúwo, ní èyí tí a gbàgbọ́ wípé ó ṣe okùnfà àwọn ipá rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí babaláwo nínú ọ̀pọ̀ eré orí-ìtàgé ilẹ̀ Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré Olókun ní 1967 Lábẹ́ àkóso Ọ̀jọ̀gbọ́n olóògbé Ọlá Rótìmí, gbajú gbajà òǹṣé orí-ìtàgé (dramatist) àti olùkọ̀tàn àdídùn ní ilé-ẹ̀kọ́ àgbà ti Ilé-Ifẹ̀ tí wọ́n sọ di Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University Bákan náà ni Peter tún jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùkọ́ ní Ilé-ẹ̀kọ́ àgbà Ilé-Ifẹ̀ ìyẹn Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University, níbi tí òun pàá pàá ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ìmọ̀ Theatre Art ní 1978..
wikipedia
yo
Òun náà tún ni ẹni tí ó kọ́kọ́ kópa gẹ́gẹ́ bíi "Pápá Ajasco", nínú sinimá àgbéléwò tí Ọ̀gbẹ́ni Wale Adénúsókè..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó tún ti kópa nínuọ̀pọ̀lọpọ̀ eré orí-ìtàgé ilẹ̀ Nàìjíríà tó lààmì laaka gẹ́gẹ́ bí Ṣàngó, tí ó jẹ́ ìtàn akọni ìgbà ìwáṣẹ̀ tí Ọbáfẹ́mi làasode gbé jáde tí Wale Ogunyemi sì ṣe àpilẹ̀kọ rẹ̀ ní ọdún 1997ìkópa rẹ̀ ́ Ṣàngó (Film) (1997)Àwọn ìtọ́kasíàwọn Ọjọ́ìbí ní 1946àwọn ènìyàn Aàyéàwọn Oṣé Ara Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ọlátúbọ̀sún Ọládàpọ̀ tí a mọ̀ sí Túbọ̀sún Ọládàpọ̀, tàbí oré ayékòótọ́ - ójí Asọ̀rọ̀-Soba (wọn bí ní ọjọ́ kọ́kàndínlógún oṣù Ọ̀wẹ́wẹ́,akéwì-Aláta jẹ́ akéwì-alohùn Yorùbá, Òǹkọ̀wé, Olóke Orin, atọ́kùn lórí rédíò, sọ̀rọ̀sọ̀rọ̀, àti olùwádìí láti orílẹ̀èdè Nàìjíríà tí púpọ̀ nínú àwọn olùgbọ́ rẹ̀ ń sọ Yorùbá tí wọ́n sì ń gbé ní ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà,ìgbésí-ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ ó lọ kọ́ṣẹ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ṣẹ́ àwọn Olùkọ́ni Luke, Ìbàdàn níbi tí ó ti kọ́kọ́ ké ewì ní ilé ẹ̀kọ́ ní ọdún iṣẹ́ ọnà 1965 (Festival of Arts), ó sún ìjálá ewì alohùn..
wikipedia
yo
O pari ẹ̀kọ́ yìí ni 1967, wọ́n sì gbe lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ St..
wikipedia
yo
Mo peregedé nínú ètò náà pẹ̀lú àmì ìpele tí ó gaju lọ..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1969, ó darapọ̀ mọ́" The Sketch newspaper Ununary, ìwé - ìròyìn Yorùbá níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ ọdún kan kí ó tó lọ sí tẹèyàn ìwò-oòrùn Nàíjíríà Western Nigerian Television (WNTV), ètò Ọ̀igbohunsafefe ìwò-oòrùn Nàíjíríà Western Nigerian Broadcasting service (WNves)..
wikipedia
yo
Ó ṣe alababọ́ọ̀lùde Adébáyọ̀ Fálétí, tí ó kó ipa pàtàkì nínú ìgbésí-ayé rẹ̀ àti ọmọba Adebayo Sanda, atọ́kùn Káàárọ̀ oòjíire àti tiwa n'tiwa..
wikipedia
yo
Oladapo fi ise sile ni odun 1977, o si da ileeṣẹ to n gbe orin jade, lati wa, se igbelaruge ati gbe awon olorin ati akewi ti won lo ede abinibi jakejado ile Yorubao ti gbe orin to le mọ́kànlélaadota ati igba olorin jade..
wikipedia
yo
Lára wọn ni olóògbé Ọ̀jọ̀gbọ́n Ogundare Foyanmu lati Ògbómọ̀sọ́, Odolaye Aremu láti Kwara, Ayanyemi Atoko wá gbowó nílé – afi-dára, Alabi Ogundepo àti Dúró Olùdiipo..
wikipedia
yo
Àwọn àwo ewì tirẹ̀ jẹmọ́ àwọn ewì àkọ́sórí tí ó di ewì alohùn..
wikipedia
yo
K-12 Voices wà lára àwọn wọ́n akọrin ẹgbẹ́ Ọládàpọ̀ ti olóògbé Diipo Sodiipo ṣe adarí orin ..Àwọn iṣẹ́ àpilẹ̀kọ rẹ̀ Ọládàpọ̀ ti gbé ìwé tí kò dín ní mọ́kàndínlọ́gbọ̀n jáde, lára wọn ni àwọn ìwé tí wọ́n dábàá fún àwọn ọmọ ilẹ̀ilẹ̀ alábẹ̀ẹ̀rẹ̀béèrè àti sekondiri títí dé Yunifásítì ní Nàìjíríà àti Òkè-òkun ..
wikipedia
yo
Òun ni òǹkọ̀wé àròyé akéwì apá kìn-ín-in àti èkejì àti arọ̀fọ̀ àwọn ọmọdé..
wikipedia
yo
Awon ere onitan/onise re Ogun làkáàyẹ ati Egbade gba ebun olubori papo ni idije ere-onise Oxford University Press ni 1970.Awon oye ibile ti won fi da a lola Oloye ni ni iluIbadan ni IpinleOyo-Ekiti ni Ipinle-Ekiti ni IpinleEkiti.Awon ebi re ebi bi awon omo ti awon naa je akewi ati onimo eda-ede paapaa julo ipinle julo Kola Tubosun ti oun naa je onimo naa je onimo isiro ati ilu òjò ni 1943 ni 1943 alààyẹ̀..
wikipedia
yo
Fermín IV ẹbọllero Eliz (ọjọ́ December, 1974), jẹ́ Mexican Adó..
wikipedia
yo
Fermín gbajúmọ̀ bẹ̀ Híni láti gangsta Rapta Ọjọ́ìbí ni 1974àwọn Olórin Rap ará Mefarakan..
wikipedia
yo
Dúró Ládípọ̀ (1931–1978) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ògúná gbòngbò olùkọ̀tàn eléré oníṣe Yorùbá tí ń dátá lẹ́nu ìgbín ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ lẹ́yìn ìmúnisìn àwọn òyìnbó..
wikipedia
yo
Àwọn ìwé àpilẹ̀kọ rẹ̀ dá lórí èdè Yorùbá, ó kọ gbogbo ohun àmúyẹ àṣà Yorùbá bí tàwọn akọni ìgbà ìwáṣẹ̀ nínú ọ̀pọ̀ ìwé àpilẹ̀kọ rẹ̀, ní èyí tí ó ṣàyípadà rẹ̀ sí àwọn ohun ìgbafẹ́, àwòrán àti sinimá àgbéléwò.Ère oníṣẹ́ ọba kò sọ (The King Did Not hang), jẹ́ ọ̀kan kànkà lára ìtàn akọni ìgbà ìwáṣẹ̀ tí ó sọ̀rọ̀ nípa bí ọba Ṣàngó ṣe di òrìṣà àkúnlẹ̀bọ, lọyin-mọmọ àdó láti Nàìjíríà títí dé àwùjọ àgbáyé pàá pàá jùlọ àwùjọ ìpẹ̀jọ́-pọ̀ àkọ́kọ́ ‘Commonwealth Arts Festival’ ní 1965 àti ní ilẹ̀ aláwọ̀ funfun pátá pátá European,níbi tí lámèyítọ́ ilẹ̀ Berlin kan, ọ̀gbẹ́ni Ulli 80 tí ṣe gbẹ̀mí ń gbé ọ wọ̀ láàrin Ládípọ̀ sí Karajan..
wikipedia
yo
Ládípọ̀ sábà ma n kópa nínú eré oníṣe rẹ̀ lọ́pọ̀ ìgbà.Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n wò Dúró Ládípọ̀ ní ìlànà onígbàgbọ́, tí bàbá rẹ̀ sì jẹ́ adarí ìjọ mímọ́ ti Àgùdà (Anglican) ní Òṣogbo..
wikipedia
yo
Àmọ́ ṣá, ó ṣe é ṣe kí Ládípọ̀ ti já ìfun baba baba rẹ̀ tí ó ṣe àtìpó wá láti Òṣogbo lẹ́yìn ogun Jálumi jẹ́..
wikipedia
yo
Bàbá yìí fẹ́ràn àwọn ìtàn akọni ìgbà ìwáṣẹ̀ pàá pàá jùlọ èyí tí ó bá ṣẹ̀ wá láti Ọ̀yọ́, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé wọ́n mọ bàbá bàbá rẹ̀ mọ́ Ṣàngó àti Ọya bíbọ̀ nígbà ayé rẹ̀.Ìrìnkèrindò iṣẹ́ rẹ̀ Ládípọ̀ gbìyànjú gidi tí ó sì lààmì laaka látàrí ìgbìyànjú rẹ̀ láti tan àṣà, ìṣẹ̀ṣe àti àkọmọ̀nà Yorùbá jákè jádò àgbáyé kódà nígbà tí ó wà ní abẹ́ àṣẹ àwọn òbí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí onígbàgbọ́..
wikipedia
yo
Nígbà ewé rẹ̀, ó ma ń yọ kúrò nílẹ̀ láti lọ wo ìran ọdún ìbílẹ̀ Yorùbá..
wikipedia
yo
Ìfara-fọkàn ṣáṣá yí ni ó jẹ́ kí ó má patú oríṣi jìlé nínú eré oníṣe orí-ìtàgé àti àwọn àpilẹ̀kọ rẹ̀ lọ́kan ò jọ̀kan..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó kúrò ní Òṣogbo, ó gbéra lọ sí Ìbàdàn, ni bi ti ó ti ń ṣiṣẹ́ Olùkọ́..
wikipedia
yo
Lásìkò tó wà ní Ìbàdàn, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀ tó dá ẹgbẹ́ òṣèré òníbárí yọyọ kalẹ̀, ní èyí tí ó sì tún ṣe ìfilọ́ ẹgbẹ́ náà ní Òṣogbo tí ẹgbẹ́ náà sí dígí àyẹ fún ìdàgbàsókè àti ìgbélárugẹ iṣẹ́ òpòlòpò àti ọ̀pọ̀ òṣèré ní ìlú lẹ́yìn tí ó ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwúrí láti ọ̀dọ̀ jíjìn Òṣogbo, Òṣogbo..
wikipedia
yo
Nínú gbogbo ìgbòkè-gbodò iṣẹ́ rè yí náà ni Dúró Ládípọ̀ ti kọ ìtàn Yorùbá mẹ́wàá tí ó kún fún orin, ìlù, ijó, òwe, ìsínjẹ àti àwọn orin ìwúrí lọ́kan ó jọ̀kan.Dúró Ládípọ̀ dá ẹgbẹ́ òṣèré tirẹ̀ ká lé ní ọdún 1961, ní èyí tó kẹ́sẹ-járí pẹ̀lú ẹgbẹ́ owú M̀báyò ní Òṣogbo..
wikipedia
yo
Ọba Wàjà (The King is Dead) ni ó fẹnu sọlẹ sọrí ìtàn tó gún gbajú-gbajà òǹkọ̀wé eré oníṣe kan tí ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Wole Soyinka tí ó fi kọ eré onítàn "Ikú àti ẹlẹ́sìn ọba” (Death and the King's Horseman.) Bákan náà ni Ládípọ̀ tún gbé eré oníṣe kan àrà ọ̀tọ̀ yọ tí ó pè níMọ́remí, eré oníṣe tó dá lórí bí akọni obìnrin ìgbà ìwáṣẹ̀ Yorùbá kan tí ó ń jẹ́ orúkọ eré onítàn náà..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ọ̀pọ̀ nínu àwọn àpilẹ̀kọ eré onítàn rẹ ti di sinimá àgbéléwò lóde òní lórí àmóhùn-máwòrán.Kódà, òun ló dá ètò bodè Wásinimi sílẹ̀ fún ilé iṣé amóhùnmáwòrán NTA (Nigerian Television Authority) ti Ìbàdàn.Ní ọdún 1977, Dúró Ládípọ̀ kópa nínú eré ìdíje ti Festac '77, ọdún ìdíje ẹlẹ́kejì irú rẹ̀ tí ó tóbi jùlọ lágbàyé tí aláwọ̀ dúdú àti funfun tí kópa tó lààmì laaka nílù Èkó.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1931àwọn Ọjọ́aláìsí ní 1978..
wikipedia
yo
Joseph Fọláhàn Ọdúnjọ (1904-1980) jẹ́ ògbóntagí òǹkọ̀wé, olùkọ́, àti olóṣèlú tí ó gbajúmọ̀ fún àpilẹ̀kọ lítíréṣọ̀ Yorùbá àwọn ọmọdé.Ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Ọdúnjọ ní ìlú Ìbarà, Abẹ́òkúta ní ọdún 1904..
wikipedia
yo
Ó lọ sí ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti ‘St Augustine Primary School', ní Abeokuta..
wikipedia
yo
Lẹ́yìn tí ó sì tún lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí 'Catholic Higher Elementary Training School’ àti ilé ẹ̀kọ́ àgbà ti 'London Institute of Education'.Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ àti òǹkọ̀wé Ọdúnjọ tẹ̀ síwájú nínú iṣẹ́ ìkọ́ni rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ ilé ìwé Catholic Training College, Ìbàdàn láti ọdún 1924 tí tí di ọdún 1927, tí ó sì padà di ọ̀gá àgbà ilé ẹ̀kọ́ rẹ̀ tó ti jáde tẹ́lẹ̀ rí ìyẹn St Augustine, Abéòkúta..
wikipedia
yo
Gẹ́gẹ́ bí olùkọ́, ó dá ẹgbẹ́ ìṣọ̀kan àpapọ̀ àwọn olùkọ́ ti ìjọ Kátólííkì (Catholic) láti lè ma bá àwọn aláṣẹ àti olóòtú àgbà sọ̀rọ̀ fún ìgbáyé gbádùn àwọn olùkọ́ wọn..
wikipedia
yo
Bákan náà ni Ọdúnjọ tún ṣe olùkọ́ àti olùkọ́ àgbà fún àwọn ilé-ìwé ìjọ́sìn Kátólííkì oríṣiríṣi káà kiri láti ọdún 1940 tí tí di 1950..
wikipedia
yo
Àwọn iṣẹ́ àpilẹ̀kọ tó ti tẹ̀ jáde láti ọdún 1958 ni ó jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú àwọn iṣẹ́ ìbẹ̀rẹ̀-pẹ̀pẹ̀ èdè Yorùbá..
wikipedia
yo
Ó tẹ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé eré onítàn ọlọ́rọ̀-geere (novels), ìwé eré oníṣe orí-ìtàgé (plays), ìwé ewì (poems) àti àkọsílẹ̀ ní èdè Yorùbá ..
wikipedia
yo
Àwọn ìwé tí ó kọ tí ó tẹ̀ jáde náà ló jẹ́ àkàsọ̀ fún àwọn òǹkọ̀wé èdè Yorùbá òde òní ní ìwúrí láti gbé àpilẹ̀kọ Yorùbá lárugẹ síwájú si..
wikipedia
yo
Ní ọdún 1966 sí ọdún 1969, ó jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú ìgbìmọ̀ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ akọ́mọ-lédè Yorùbá Orthography..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ olùkọ́ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (Nigeria Union of Teachers) fún àìmọye ọdún.Ṣíṣe òṣèlú rẹ̀ ní ọdún 1951, ó di ọmọ ilé aṣòfin ti (Western House of Assembly) tí ó sì tún padà di Mínísítà àkọ́kọ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ àti iṣẹ́ ṣíṣe ní ìwọ̀ Oòrùn Nàìjíríà (region's first minister of land and Labour).Bákan náà ni ó tún ṣe Ààrẹ fún ọmọ ẹgbẹ́ Ẹ̀gbádò (Ẹ̀gbádò Union) tí wọ́n sì tún fi jẹ́ oyè aṣíwájú gbogbo ilẹ̀ Ẹ̀gbá pátá.Joseph Fọláhan Ọdúnjọ di olóògbé ní 1980.Àwọn iṣé àkànṣe rèéwí iṣẹ́ ní ogún isẹ́ ("Work is the antidote for Poverty") tójú ìwà rẹ̀ ọ̀rẹ́ mi ("Watch Your behaviour, my friend") (1961)Ìtàn àròkọ ọlọ́rọ̀-geere ọmọ òkú ọ̀run (1964; "The deceased woman's daughter") àkàyé àwọn ìtọ́ka sí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1904àwọn Ọjọ́lẹ ní 1980..
wikipedia
yo
Ìsàlẹ̀ Èkó (Lagos Island) jẹ́ àárín gbùngbùn agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ , Ìpínlẹ̀ Èkó..
wikipedia
yo
O jẹ okan lara ijoba ibile ti won pin ipinle Eko si..
wikipedia
yo
Nínú ètò ìkànìyàn tó wáyé ní ọdún 2006 nílẹ̀ Nàìjíríà, ìjọba ìbílẹ̀ náà ní ìwọ̀n èrò tó pọ̀ tó 209,437 ní agbègbè tí kò ju ìwọ̀n ibùsọ̀ 8.7km km ..
wikipedia
yo
tí ó tóbi tó nã kọjá lórí àfonífojì Èkó tí ó fi dé Èbúté Mẹ́ta..
wikipedia
yo
Ọ̀pọ̀ ẹbí ni ó ń gbé ní ibùgbé tí wọ́n ń pè ní Broad Street ní Marina.Apá àríwá ìsàlẹ̀ Èkó ní ọ̀pọ̀ ilé òun ọjà tí kò gbòòrò wà tí ó sì ma ń sábà kún fọ́fọ́ fún èrò tí ẹsẹ̀ kò sì gbèrò níbẹ̀..
wikipedia
yo
Ìjọba ti ń gbìyànjú láti kọ́ àwọn ọ̀nà tún tún síbẹ̀ lọ́nà àti le mú àdínkù bá súnkẹrẹ fàkẹrẹ ojú pópó náà kí ọkọ̀ lè má lọ gààràgà..
wikipedia
yo
Ó tún jẹ́ apá ibi tí ọba Èkó ń gbé (King of Lagos)..
wikipedia
yo
Bákan náà ni ó jẹ́ ìgbàgbọ́ pé apá agbègbè yìí nìkan ni ọdún ẹyọ ti lè wáyé ní ìpínlẹ̀ Èkó.ètò ọrọ̀ ajé ọ̀pọ̀ ilé ìfowó-pamọ́ ni ó ní olú ilé-iṣẹ́ wọn ní Ìsàlẹ̀ Èkó, ní èyí tí ilé ìfowó-pamọ́ ima PRṣùtá i ṣíraFirst Bank of Nigeria jẹ́ ọ̀kan lára wọn tí ó ní olú ilé-iṣẹ́ rẹ̀ ní Marina..
wikipedia
yo
Ilé ìfowó-pamọ́ mìíràn tí ó tún ní olú ilé-iṣẹ́ níbẹ̀ ni ilé ìfowó-pamọ́ UBA (United Bank for Africa)..
wikipedia
yo
Lọlá Ògúnnáìkè jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tún jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà (American) tí ó jẹ́ amúlùúdùn àti oníròyìn ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀ wọ́n bí Lọlá ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹsàn ọdún 1975 (September 13, 1975) ní ìlú New York City àmọ́ àwọn òbí rẹ̀ méjẽjì jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Ó gba oyèkọ́ ẹ̀kọ́-kejì nínú iṣẹ́ ìròyìn ní ilé-ẹ̀kọ́ àgbà ti New York University , nígbà tí òye ó ti kọ́kọ́ gba oye ìmọ̀ àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Lítíréṣọ̀ Gẹ̀ẹ́sì (English Literature) nílé ẹ̀kọ́ àgbà University of Virginia.Ìgbòkè-gbodò iṣẹ́ rẹ̀ Ògúnnáìkè bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí oníròyìn ní ọdún1999 nípa ṣíṣe ìròyìn amúlùúdùn àti àwọn àṣà míràn tó bá jẹ yọ..
wikipedia
yo