cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
L'ati ọdun 1988 si ọdun 1992, o jẹ onimọran (onimoran ofin ati ẹjọ) si Agbẹjọro gbogboogbo (Attorney General) ati Minisita fun Ìdájọ́, Bola Ajibola.. | wikipedia | yo |
Osinbajo bere ise olukoni ni omo odun metalelogun.Lati odun 1997 si odun 1999, won so Osinbajo di ojogbon ninu imo ofin ati olori eka ofin ti gbogbo eniyan ti eka ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ ofin ni Yunifasiti Eko.. | wikipedia | yo |
Lati odun 1999 si odun 2007, Osinbajo je omo egbe igbimo ile ise idajo ti Ipinle Eko.. | wikipedia | yo |
Ni odun 2007 bakan naa, won fi Osinbajo je oga alábàáṣepọ̀ ti awon alábàáṣepọ̀ SimmonsCooper (awon Amofin ati awon agbejoro) ni Naijiria.. | wikipedia | yo |
Osinbajo tun jẹ olukọni agba ni Yunifasiti ti ipinlẹ Eko.. | wikipedia | yo |
Oun tun ni Agbẹjọro gbogboogbo (Attorney General) ati KọnaNàìjíríà fun eto idajo .. | wikipedia | yo |
L'ati odun 2007 si odun 2013, Osinbajo tun gba ise gege bi i ojogbon onimo ofin ni Yunifasiti Eko.ise oluṣọ aguntan Yemi Osinbajo ni oluṣọ aguntan ti o n se amojuto ẹkun ile ijosin ikeji-din-l'aadọta ti igi Obaí (Olive Tree Prospects Headquarter) ti Ijo Ìràpadà ti Kristi ti o wa ni ilu Eko.Igbakeji Aareigba akokoawon idibo odun 2015 lehin ti won se idasile egbe Onigbaa (All Progressive Congress) ni odun 2013, won fun Yemi pelu u awon olokiki omo ile Naijiria miiran ni ise lati se agbekale akosile awon eto ati oun ti egbe tuntun yi i ma a mulo.. | wikipedia | yo |
Eleyí i ló yọ'ri sí àkójọpọ̀ tí wọ́n pè ní "Ìlànà sí Nàìjíríà tuntun", èyí ni ìwé àkọsílẹ̀ kan ti ẹgbẹ́ onígbaa (All Progressive Congress) ke'de rẹ gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ètò àti iṣẹ́ tí ẹgbẹ́ yí i má a ṣe nígbà tí wọ́n bá yàn wọ́n sí orí i àlèéfa.. | wikipedia | yo |
Àwọn ohun pàtàkì nínú un Ìlànà yí i ni ètòt oúnjẹ ọ̀fẹ́ fún àwọn ọmọ ilé ìwé, fifi owó ránṣẹ́ pẹ̀lú u gbé-ń-dèké (ohunránṣẹ́ cash transfer) sí mílíọ̀nù mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n àwọn aláìní jù lọ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n bá fi orúkọ ọmọ wọn sí'lẹ̀ l'àti lo ilé ìwé, tí wọ́n sì tún gba abẹ́rẹ́ àjẹsára fún wọn.. | wikipedia | yo |
Awon oniruuru u anfaani eto si oro aje fun opolopo odo omo Naijiria ni o tun wa.Ni ojo ketadinlogun odun 2014, oludije fun Aare l'abe e egbe e Onigbaale (All Progressive Congress), Ọ̀gágun-fẹhinti Mohamìyàsímímọ́ Buhari Ke'de Osinbajo gege bi i amugbalegbe e re ati oludije fun igbakeji Aare fun idibo gbogboogbo ti odun un 2015.. | wikipedia | yo |
Ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kẹta (oṣù Ẹrẹ́nà) ọdún un 2015, Àjọ tí ó ń rí sí ètò ìdìbò jẹ́rĩ í sí yíyan Buhari gẹ́gẹ́ bí i ẹni tí ó bọ́'rí ìdìbò ti Ààrẹ.. | wikipedia | yo |
Bayi i ni Osinbajo se di igbakeji Aare ti a d'ibo yan fun orile ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bú'ra fún àwọn méjèèjì ní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn ún (oṣù Èbìbì) ọdún 2015.. | wikipedia | yo |
Ni ojo ketadinlogun osu kejo (osu ogun) odun 2017, igbakeji Aare Yemi Osinbajo se apejuwe oro ikorira gege bi i eya ipanilaya.akoko Yemi Osinbajo da'wo le ise gegegege bi i igbakeji Aare orile ede Naijiria ni ojo kokandinlogbon osu karun un ni gbagede ti Eagle Square ni Abuja.. | wikipedia | yo |
Ojúṣe rẹ ni l'ati bojuto ati l'ati royin nipa ẹgbẹ ti o n ri si etot ọrọ aje, ki o si se eto nipa igbani iyanju lo si ọdọ ija Aare, eni ti yi o mu ipinnu wá gbẹ̀hìn.. | wikipedia | yo |
Gẹ́gẹ́ bí i ìpínlẹ̀ e rẹ̀ níinú ìmọ̀ o òfin àti ìrírí i rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i kọ́natẹ́lẹ̀ fún ètò ìdájọ́ ní ìpínlẹ̀ Èkó fún ọdún mẹ́jọ, ọ̀pọ̀ ènìyàn l'èrò pẹ́ yí ọ k'ọ̀pá tó jọ'ju nínú u àtúnṣe tí a ní'lọ ní'nú ètò òfin orí'lé èdè ẹ wá.. | wikipedia | yo |
Nígbà tí ẹgbẹ́ onígbaale (All Progressive Congress) ń polongo fún ibo ní ọdún 2014/15, Yemi Osinbajo se opolopo ipade pelu awon ara ilu yika orile ede ni ilodi si Ipọlọ-n-go gba-n-gba ti ọ̀pọ̀ ọmọ orí'lé èdè Naijiria oun olóṣèlú u won ma a ń ṣe tele.. | wikipedia | yo |
Ọ̀kan nínú àwọn ìlérí tí ó ṣe ní’gba ìgòpọ̀-n-gọ̀ ìbò, tí ó sì tún sọ láìpẹ́ yìí ni ti ètò l'àti fi oúnjẹ ẹ̀ẹ̀kan l'ojúmọ́ bọ́ ọmọ ilé ìwé kọ̀ọ̀kan.. | wikipedia | yo |
Yàtọ̀ sí fífún ọmọ ilé ìwé ní oúnjẹ, ó tún tẹ̀'nú mọ́ láìpẹ́ pé ètò yìí yo ó pèsè oríṣiríṣi iṣẹ́ (ìlérí ìgòpọ̀-n-gọ̀ ìbò míràn) fún àwọn tí ó bá dà’rà pọ̀ l'àti s'iṣẹ́ l'abẹ́ ẹ̀ ètò yìí l'àti mú wá sí ìmúṣẹ.adelé Ààrẹ Ààrẹ Muhammadu Buhari kọ́ àkọsílẹ̀ ní ọjọ́ kẹ́sà oṣù karùn-ún ọdún 2017 sí Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà àti ti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kékeré lórí i ìpinnu rẹ̀ láti bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò fún ìtọ́jú àìlera rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ka ìwé yí i ní ọjọ́ kẹsàn án oṣù karùn ún ọdún 2017 ní ibi àpérò àwọn ilé méjèèjì, ti aṣòfin àgbà àti ti kékeré ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀lé.. | wikipedia | yo |
Igbakeji Aare, ojogbon Yemi Osinbajo ni won jíròrò le so di adele Aare fun akoko ti Aare Buhari yi o o fi wa ni isinmi nitori i ailera re.Ni ojo keje osu kejo odun 2018, Osinbajo yo oga agba ti o n ri si aabo ara ilu, Lawal Daura kuro l'enu ise fun wiwo ile asofin ti awon ti o di ihamọra ogun pelu u iboju l'ati eka ile ise re wa a ni ona ti ko to.. | wikipedia | yo |
Daura ni won ti fi Mathew Seiyefa ro'po o re.akoko kejikíkéde ete lati dupo àárẹ̀ni ojo Kọkànlá, osu kerin, odun 2022(April 11, 2022), Igbakeji Aare, ojogbon Yemi Osinbajo kede ete re lati dupo Aare Naijiria ni odun 2023 labẹ egbe oselu APC, o pada fi idi rẹmi si ipo keta ninu idibo abe APC.Awon itọkasiawon igbakeji Aare ile Naijirimeje agbejoro agba ile Naijiriàwọn eniyan alààyèawon Ọjọ́ìbí ni 1957.. | wikipedia | yo |
O ni orilẹ-ede ilẹ tobi ibudo.itọkasi oṣiṣẹ aaye ayelujara awọn ilu Israẹli.. | wikipedia | yo |
Richard Claxton Gregory (Ọjọ́ Kejìlá Oṣù Kẹwa Ọdún 1932 - Ọjọ́ ọ̀kàndínlógún Oṣù Kẹjọ Ọdún 2017) jẹ́ aláwàdà, alákitiyan ètò aráàlú, alárìíwísí, Olukọwe, oníṣòwò, àti òṣèré ará Áfíríkà bí Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Hardee's jẹ Amerika ounje ti ko ni iye owo ti o bere ni 1960.. | wikipedia | yo |
Àwọn ilé títà ta àwọn ègé adìẹ, Frites àti àwọn hamBurgers.. | wikipedia | yo |
Kazuo Ishigurọ (ojo osu Kọkànlá 1954) je Olùkọ̀wé to gba ebun Nobel ninu Litireso ni odun 2017.Ìtọ́kasí }awon ẹlẹ́bùn Nobel ninu Litireso.. | wikipedia | yo |
Lester speight (Ọjọ́ìbí Oṣù August 28, 1963) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ralph Düren "ralphìe" May (ọjọ́ìbí Oṣù February 17, 1972) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Andrew Geoffrey "Andy" Katọ́jú (ọjọ́ Oṣù January 17, 1949) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Christina Ricci (ọjọ́ìbí Oṣù February 12, 1980) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn òṣèré ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Cameron Arthur "cam" Clarke (November 6, 1957) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn òṣèré QFIVI ará AMẸ́RÍKÀ.. | wikipedia | yo |
Moira Kelly (Ọjọ́ìbí March 6, 1968) jẹ́ òṣèré ara Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Donald John Trump (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlá osu kẹfà ọdún 1946) ni Ààrẹ orílẹ̀ èdè Amerika Ẹlẹ́ẹ̀karùn lọ́wọ́lọ́wọ́ 45k, O gori alefa ni ogúnjọ́, oṣu kìíní ọdún 2017.. | wikipedia | yo |
Trump jẹ́ gbajúgbajà oníṣòwò kí ó tó dara pọ̀ mọ́ òsèlú.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
(December 14, 1960) je agbejoro ara Amerika to sise tele bi oludari Federal Bureau of Investigation ilẹ̀ Amẹ́ríkà.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn ara Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Anna Netrebko (Ọjọ́ìbí 18 September 1971, òmìnirad (Ìṣọ̀kan Sofi)) je olorin omo ile Russia.Àwọn Ọjọ́ìbí ni 1971.. | wikipedia | yo |
(Ọjọ́ìbí September 25, 1968) jẹ́ òṣèré, olóòtú, Jóṣúà, aláwàdà àti akọ-orin ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ni osu April 2007, Newsweek pe ni “oṣere to lágbárajulọ ni Hollywood” | wikipedia | yo |
Smith ti jẹ́ yíyan fún Ẹ̀bùn Golden Globe marun ati ẹ̀bùn Adèmí meji, bẹ́ síni ó ti gba ẹ̀bùn Grammy mẹrin.Ìtọ́kasí òṣèré fíú ara Américo won osere tẹlifíṣàn ara Amékàáwọ́n Aláwàdà ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Michael Chadefya ṣátá (6 July 1937 – 28 October 2014) jẹ́ olóṣèlú ará ilẹ̀ Zambia tó jẹ́ ààrẹ ilẹ̀ Zambia ìkarùn, láti 23 September 2011 títí tó fi kú ní 28 October 2014.. | wikipedia | yo |
Olóṣèlú àwùjọ ni, ó léwájú ẹgbẹ́ òṣèlú Patrioc Front (Columbia), ní Zambia.. | wikipedia | yo |
Lábẹ́ Ààrẹ Frederick Chmìpé, ṣátá jẹ́ àpapọ̀ ètò ní ẹ̀wádún 1990 gẹ́gẹ́bí ìkan lára àwọn tó ṣe ìjọba movement for Multipa Democracy (mmd—ìtọ́kaeìtọ́ka Ààrẹ ilẹ̀ Sámbíà.. | wikipedia | yo |
Jerzy Oskar StuHR (Ọjọ́ìbí 18 April 1947) jẹ́ òṣèré Ara Pókẹ́ta.Ìtọ́kasí Ara Poikùn00.. | wikipedia | yo |
Gabrielle Monique Union-Wade (born October 29, 1972) jẹ́ òṣèré aré Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí òṣèré tẹlifísàn Ara Américo òṣèré Kanú fíu Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Tracée Ellis Ross (orukọ àbísọ Tracée Joy Silberstein; October 29, 1972) jẹ́ òṣèré, ológe, aláwàdà àti olóòtú ètò agbọ̀n tó gbajúmọ̀ fún eré rẹ̀ bi Dr.. | wikipedia | yo |
Rainbow Johnson lórí eré ìtara ilé-iṣẹ́ Opín ABC Black-já-tracee Ellis Ross jẹ́ ìkan nínu àwọn ọmọ Diana Ross.Ìtọ́kasí àwọn òsèré ara AmeriÌyọnuwon òsèré ara Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
(Ibi June 7, 1943) je ako-ewi, Olùkọ̀wé, Alatusọ, alákitiyan, àti olùkọ́ ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Ìkan nínú àwọn akọewì tó gbajúmọ̀jùlọ lágbàyé, nínú àwọn ìṣe rẹ̀ ni àwọn ìwé ewì, àwo-orin ewì, àti àwọn àyọkà oríṣiríṣi tí wọ́n dá lórí ẹ̀yà, ọ̀rọ̀ àwùjọ àti ìwé ọmọdé.. | wikipedia | yo |
O ti gba ọpọlọpọ ẹbun, ninu wọn ni ẹbun ẹṣọ Langston Hughes, ẹbun eniyan NAACP.. | wikipedia | yo |
Wọ́n ti yàn fún ẹ̀bùn Grammy, fún Awo-orin rẹ̀ The Nikki Giovanni Poetry Collection.\Ìtọ́kasíàwọn ọmọ Áfríkà Amél Olukọwe ará ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Sean John Combs (Ọjọ́ìbí November 4, 1969), To tún gbajúmọ̀ pèlú àwọn orúkọ ìtàgé rẹ̀ puff Ìlàn, Puffy, p.. | wikipedia | yo |
Diddy, ati Diddy, jẹ olorin Rap, akọrin, Akowe-orin, oṣere, àkọ̀tun awo-orin ati oniṣowo ara Amẹrika.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí ní Harlem, ó sì dàgbà ni Mount Vernon, New York.. | wikipedia | yo |
Ó ṣiṣẹ́ bí olùdarí tálẹ́ntì ni uptown Records kò tó dá ilé-iṣẹ́ tí ẹ bad Boy entertainment sílẹ̀ ní 1993.. | wikipedia | yo |
Àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́ No Way Out (1997) ti gba ìwé ẹ̀géè Platityl meje.. | wikipedia | yo |
Combs ti gba ebun Grammy meta ati MTV Video Music Award meji, ohun si ni atọ́kùn ètò ìlú MTV Making the band.. | wikipedia | yo |
Ni 2017 Forbes sọ pé ọ̀la rẹ̀ tó $820 million.Mosekakún Àwọn olórin Rap ará Américo ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
TuKur Yusuf búrata (ọjọ́ìbí 24 Oṣù Kọkànlá 1960) jẹ́ igbákejì Ọ̀gágun ará Nàìjíríà àti ògá àwọn Ọmọsẹ́ Agbógun ilẹ̀ Nàìjíríà lọ́wọ́, ipò tí Ààrẹ Muhammadu Buhari yàn sí ní oṣù keje 2015.. | wikipedia | yo |
Ó gba ipò ológun ní 1983, Látìgbà nà ó ti ṣiṣẹ́ ní ipò orírírí bí ọ̀gá, aláròyìn àti ìkọ́nijùpọ̀. Ọmọ ológun Ara Nàìjíríààwọn ọ̀gágun ara Nàìjíríààwọn ọ̀gá Ọmọ̀n Agbógun Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Joseph Ahan (12 April 1937 – May 1968) jẹ́ ògá Ologun ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti oṣù karùn ọdún 1967 sí karùn ọdún 1967, tí ó sì kú látàrí ìjàmbá ọkọ̀ òfúrufú tí ó wáyé nígbà ogun abẹ́lé Nàìjíríà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ọ̀gágun ará Nàìjíríààwọn ògá ọmọsẹ́ Agbógun Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Theophilus Yakubu Danjuma Gcon fss òróró (ọjọ́ 9 December 1938) jẹ́ ọ̀gágun tó ti fẹ̀yìntì, olóṣèlú àti oníṣòwò ará Nàìjíríà láti ẹ̀yà Júkún.. | wikipedia | yo |
O je oga ọmọṣẹ́ Agbógun Naijiria lati July 1975 de October 1979.. | wikipedia | yo |
Ó sì tún jẹ́ àpapọ̀ ọ̀rọ̀ abo lábẹ́ ìjọba Olusegun Obasanjo.. | wikipedia | yo |
Danjuma ni Alaga ile-iṣẹ South Atlantic Petroleum (sápẹ́tro).àwọn ọmọṣẹ́ ologun ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Aliyu Mohammed gusau (ojoibi May 18 1943) Oga Agbógun Ara Nàìjíríà to ti feyinti.. | wikipedia | yo |
O ti je alakoso oro abo, onimoran oro abo orile-ede fun Aare Naijiria otooto meji, oga awon ọmọṣẹ́ Agbógun, o se olori fun orisirisi ile-ise Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́, besini o tun se oga alase Nigerian defence Academy.itọkasiÀwọn ọmọṣẹ́ ologun ara NaijiriLórí ogagun ara NaijiriLórí oga oga Agbógun Naijiria.. | wikipedia | yo |
Luka Nyeh Yusufáwọn ìtọ́kasíàwọn Ọmọsẹ́ Ológun ará Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
AbdulRahman Bello Dmbazau (ojoibi March 14, 1954) jẹ́ ológun pẹ̀lú okùn Ọ̀gágun onigbakeji to ti fẹyìntì lati Agbógun Ara Naijiria àti Lọ́wọ́lọ́wọ́ Alakoso ètò abẹ́lé Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Dambazau ṣiṣẹ́ bí ọ̀gá ọmọṣẹ́ Agbógun Nàìjíríà (Coas) laarin 2008 ati 2010, nigba to gbeyin Ọ̀gágun onigbakeji Luka Yusuf.Ìtọ́kasí Ọ̀gágun ará Nàìjíríààwọn Oga oga ọmọṣẹ́ Agbógun Naijiria.. | wikipedia | yo |
Azubuike Iherikarika, CFR (ọjọ́ February 13, 1956) jẹ́ igbákejì Ọ̀gágun Agbógun Ara Nàìjíríà tó ti ti feyintiati Oga àwọn Ọmọsẹ́ Agbógun tẹ́lẹ̀.Ìtọ́kasí Ọmọsẹ́ Ológun Ara Naibọ̀wọ̀ Ọ̀gágun Ara Nàìjíríààwọn Ọ̀gá Ọmọsẹ́ Agbógun Naijiria.. | wikipedia | yo |
Oga awon omose Agbógun tàbí Oga Ọmọya Agbógun lasán (Chief of Army Staff ní Èdè Gẹ̀ẹ́sì) ni Ipò tó Gajulo Òṣìṣẹ́ Ológun ni Ibirún Agbógun ará Nàìjíríà.The position is often occupied by the most senior commissioned officer appointed by the commander-in-Chief of the Armed forces of Nigeria.The Chief of Army Staff Reports to the Chief of defence staff, who also Reports to the defence Minister.The Stagitory Duty of the officer is to sọ̀rètílate and execute Policies towards the highest Attainment of National Security and operati Valnce of the Force.Àwọn Oga àwọn Agbógun ará Nàìjíríà is a ological List of Officers Holding the position of General Officer commanding (go—go) or Chief of Army Staff (CO-as).Ẹ tún wo àwọn Agbógun Ara Nàìgboka Army Army Armyments.. | wikipedia | yo |
Ella Josephine Baker (December 13, 1903 – December 13, 1986) jẹ́ Aláwọ̀dúdú ará Amẹ́ríkà tó jẹ́ alákitiyan ètò aráàlú àti ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tí a bí ní Ìpínlẹ̀ Virginia, ṣùgbọ́n tó dàgbà ní ìpínlẹ̀ North Carolina tó sì parí ẹ̀kọ́ gíga rẹ̀ níbẹ̀, ó ṣiṣẹ́ ní ọ̀pọ̀ gbogbo ilé-ayé rẹ̀ ní Ìlú New York.. | wikipedia | yo |
Ó fibẹ̀ ṣíṣe lẹ́yìn àgọ́ níbi tó ti ń ṣe alàgbàjọ fún bí ọgọ́rùn ọdún.. | wikipedia | yo |
Be sìni ó jẹ́ atọ́nà fún Diane Nash, Stokely CarMichael, Rosa Parks, àti Bob Moses.Ìtọ́kasíàwọn ọmọ Afrika Amerikááwọn Aat ara Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Luis Guillermo solis Rivera (ọjọ́ 25 April 1958) jẹ́ olóṣèlú Ara Kabe Rẹrika tó jẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ Ààrẹ ilẹ̀ Kota Rẹ̀rika lati 2014. Ara ilẹ̀ Kabeta Rẹ̀fu | wikipedia | yo |
Andrew Michael Holness, on, MP (born 22 July 1972) jẹ́ olóṣèlú ará Jàmáíkà tó jẹ́ lọ́wọ́lọ́wọ́ Alakoso agba ilẹ̀ Jàmáíkà lati 3 March 2016, lẹ́yìn ìdìbòyan gbogbogbòò 25 February 2016.Ìtọ́kasí àwọn èpọ̀ ilẹ̀ Jàmáíkà lati | wikipedia | yo |
Giannis Hugo Adéìsìnkú tàbí Antokámpo (, ; Ọjọ́-ibi K-6 Oṣù Kejìlá ọdún 1994) jẹ́ ọmọ Yorùbá àgbà Bólú-alápẹ̀rẹ̀ ará ilé kàlé..’ | wikipedia | yo |
AdeTokunbo Ungba Bbo-Mikan fún Milwaukee Kobucks ní NBA ní Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà. Gọ̀gád àwọn ọmọ Yorùbá.. | wikipedia | yo |
Cicely Louise TYson (ojoibi December 19, 1924) jẹ́ òṣèré fíú àti orí-ìtàgé ará Amẹ́ríkà.Ẹbí òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Frances Natanid Welsing (orukọ àbísọ Frances Luella ìṣed; March 18, 1935 – January 2, 2016) jẹ́ oníròyìn ọ̀kan ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Àwòko rẹ̀ tó kọ́ ní ọdún 1970, The ìṣe Theory of Colo-contation and Racism (White SupreCY), jẹ́ ìwé tó ṣe pàtàkì nípa ìtumọ̀ ìwà ìojusajú àwọn àalámọ̀.Awon ìtọ́kasíàwọn ìkọwe ara Ameriseewon Aat ará Améka ará Afrika AMẸ́RÍKÀ.. | wikipedia | yo |
Rosie Stephenson-Goodknight, tí a tún mọ̀ sí Rosiestep ní Wikipedia jẹ́ olótu Wikipedia ọmọ ìlú Amẹ́ríkà tí ó gbìyànjú lati rí wípé ojú opo imo ofe yìí jẹ́ oun tí tako tabo a ma a dásí tí ó sì ṣe àgbékalẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ètò tí ó jẹ́ kí iye àwọn àyọkà nípa obìrin tó pọ̀ṣù pọ̀ síi.. | wikipedia | yo |
ó ti kọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àyọkà tí ó sì gba ẹ̀bùn kóríyá Wikipedia ti ọdún 2016.Àwọn ìtọ́kasíàwọn ènìyàn aláàyè.. | wikipedia | yo |
ìyárí Afam fẹ́ agbára àti ogun awo ọmọ àti dúró jayé.. | wikipedia | yo |
Afam, Ahmadi, Amara, Emeca, HaLim, Isa, MMadu, Fasi, Nnamdi, nne, Owáwá, RuQret orúkọ àwọn ọmọ ìyárí afàm... | wikipedia | yo |
Gilbert "Gil" Scott-Héron (April 1, 1949 – May 27, 2011) jẹ olorin Soul ati elewi Jazz,, ati Olukọwe, to gbajumọ àgàgà fun iṣẹ rẹ bi onídán ọrọ siso.Ìtọ́kasí olorin ara Amẹrika.. | wikipedia | yo |
Simon Shelton (Bii ojo kejidinlogbon osu kínín odun 1966) je osere Geesi.Àwọn Ọjọ́ìbí ni 1966awon eniyan Alààyè | wikipedia | yo |
Nicola Jane "Nikagbára" Smedley (bíi October 1970) jẹ́ òṣèré Gẹ̀ẹ́sì.Àwọn Ọjọ́ìbí ni 1970àwọn ènìyàn Alààyè | wikipedia | yo |
púi fan Lee (bíi July 1971) jẹ́ òṣèré Gẹ̀ẹ́sì.Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1971àwọn ènìyàn òkẹrin.. | wikipedia | yo |
Chidinma Ebàále (Ọjọ́ìbí 2 May 1991), to gbajumo pelu oruko-itage re ni Chidin, je akorin ati olorin ati olorin ara ile Naijiria.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2010 ni ìràwọ̀ rẹ̀ kọ́kọ́ yọ nígbà tó gba ipò kini lórí ètò ìnà tó ń jẹ́ Project Fame West Áfríkà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀chi ní EBOlè wọn bí ní àrí Ketu ní Kosofe ní ìpínlẹ̀ Èkó .. | wikipedia | yo |
Chidinma jẹ ọmọ kẹfa ninu ọmọ meje ti àwọn òbí ẹ bi.. | wikipedia | yo |
Chidinma gbe pelu baba to mojuto ọmọ, ati ibe Lọti ko orin lati omo odun mefa.[10]Ni igba ti o di omo odun mewa, odarapo mo egbe akorin ni ile ijosin.[11] Chidinma losi ile iwe girama ti o wa ni Ketu ni ibi ti oti bere ile iwe akobere ati girama to ti pari.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn ìgbà tí óparí ilé ìwé gíga oní ìwé Mẹ́fà , ó darapọ̀ mọ́ àwọn tí wọ́n gbé owó sí Ta(Promoter) tí ó sì dára pọ̀ mọ́ Fame West Africa .. | wikipedia | yo |
Chidinma kókó lo ka ìwé ìròyìn ṣùgbọ́n ó padà lọ́kà sociology ní ilé ẹ̀kọ́ gíga Fásitì Èkó.. | wikipedia | yo |
Ni igba ti [12] Chidinma, ninu ibẹrẹ fọhùn(Interview) pelu YNaija, osofun won pe metaorin o ki se tọ̀hún sugbon ni igba ti ohun ti ja we bori ninu idije orin.Ìtọ́kasí ara Naijiria aráawọnawọn akorin ara Naijiria.. | wikipedia | yo |
Viktor Sururuv (Oṣù Kọkànlá Ọjọ́ Kẹwa, 1951) jẹ oṣere ara Russia.. | wikipedia | yo |
Ìdábẹ́ fún ọmọbìrin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ àṣà tí wọ́n ti fòfin de.. | wikipedia | yo |
Ààrẹ tẹ́lẹ̀ Goodluck Ebele Jonathan buwọ́ lu òfin ti ó fòpin si àṣà yi ni oṣù karun ọdún 2015.. | wikipedia | yo |