cleaned_text
stringlengths
6
2.09k
source
stringclasses
2 values
language
stringclasses
1 value
Wọ́n bíi pẹlu ara pípé, ìṣẹ̀lẹ̀ ijamba oko tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 1998 ni ó sọ ọ́ di alábò ara tí wọ́n fi gé ẹsẹ̀ rẹ̀ ..
wikipedia
yo
Bàbá rẹ ṣe àkíyèsí wípé ó lè fẹ́ ṣeré ní ìgbà tí ọwọ́ rẹ bá dilẹ̀, ó sì gbàá ní ìyànjú wípé kí ó mú eré ìdárayá gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ àṣelà..
wikipedia
yo
O darapọ mọ ẹgbẹ ere idaraya awọn ti ko lẹsẹ ni dimila.awọn itọkasi..
wikipedia
yo
Jolin tsai (orúkọ àbísọ tsai i-ling Ọjọ́ìbí September 15, 1980) jẹ́ olórin ọmọ ilẹ̀ Taiwan.itokáì..
wikipedia
yo
Muyiwa Ademola (A bi ní ojo kerindinlogbon, osu ṣẹ́ẹ́rẹ́ odun 1971) je ogbontarigi osere ati oludari sinima agbelewo omo Yoruba lórílẹ̀ Naijiria..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2005, fíìmù rẹ̀ orí gba àmì-ẹ̀yẹ eré abí tó dára jù lọ ní 1st Africa Movie Academy Awards..
wikipedia
yo
Ní ọdún 2008, wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèrékùnrin abí tó peregedé jùlọ..[1]Ìbẹ̀ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ìgun-ayé bí Muyiwa Ademola ní Ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù Seere, 1971 ní ìlú Abẹ́òkúta , tíì ṣe Olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ògùn Ògùn ní Nàìjíríà.[1]
wikipedia
yo
David's High School ní mọ́lẹ̀te ní Ibadan ibi tí ó ti gba West Africa Secondary School Certificate.[2]
wikipedia
yo
Ó tẹ̀síwájú sí Yunifásítì ìjọba àpapọ̀ ti ìlú Ìbàdàn ibi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ ẹ̀kọ́ àgbà (b.Ed) in adult education..
wikipedia
yo
.Ẹ.íṣe Muyiwa Ademola ti ipasẹ̀ Charles Olùmọ ti a mọ si Àgbákò tí ó fi ìlú rẹ̀ Abeokuta ...
wikipedia
yo
Ní ọdún 1995, ó gbé eré rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde tí ó pè ní àṣìṣe..
wikipedia
yo
Láti ọdún 1995, ó ti gbé, darí àti hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré Yorùbá..
wikipedia
yo
Ní tíṣà ọdún 2013, ìròyìn sọ pé ó ní ìjàba ọkọ èyí tí ó kú díè kí ó mú ẹ̀mí rẹ̀ látarakú rẹ̀.àwọn fíìmù tí ó ti kópa àti àṣìṣe (1995) ilẹ̀ orí orí àmì ayò Tolu dára ire Iranṣẹ Àrú kò “FA jání ésì wo wo 4th Africa Movie Academy Award Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1953àwọn ènìyàn Àááyàn àwọn òṣèré..
wikipedia
yo
'Sikiru Adeade ti o lọ́gbà laarin odun 1971 si ojo kejo, osu keji odun,2016), ti opolopo mo si Aragudu, je osere omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
[1] Ó jẹ́ gbajúgbajà nípa kí kópa gẹ́gẹ́ bi ìtọ́jú, ọlọ́ṣà tàbí ògbóǹtarìgì aláwọ̀ nínu àwọn fíìmù tí ó ti kópa.[2]Ní ọjọ́ kẹjọ, Oṣù kejì ọdún ẹgbàá-lé-mẹ́ẹ̀dógún ni ó ṣàìsí ní ilé rẹ̀ ní Kàdúná, apá iha Ariwa Nàìjíríà.[4][4] Fíìmù tí ó ti kópa témi ní, tí ẹ kò ìdùnú mi ìlú gangan ìgbógbó ìyá ojú ogún eré àgbèrè gbìrí ogun agba idagbo gbogbo ó ọkọ oko Bournlú ìgbà òwúrọ̀ Ayaba Olian A ọ̀rọ̀ fi ojú òdara ní Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1971àwọn òṣèré abẹ abẹ Unta E-kò ní ọjọ́ ní 2016..
wikipedia
yo
Alhaji kaka Adepoju ti opolopo mo si "Baba Wande" je osere, ònkọ̀tàn ati oludari sinima agbelewo omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Ìràwọ̀ rẹ̀ tàn nídò àwọn òṣèré tíáta nígbà tí ó kópa olóyè tún nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ n "tí wà nílẹ̀”.àwọn fíìmù tí ó ti kópa tí OLUWA ní ilé ayò ní mo fẹ́ ọdún líní ìgbékùn òjígún Ogúnlé Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn Àáàwọn òṣèré Yorùbá..
wikipedia
yo
Kunle Afolayan (ti atun mo si Ade Love) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, òṣèré àti olùdarí sinimá-àgbéléwò lédè Yorùbá..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ arákùnrin sí òṣèré Tóyìn Afọláyan, bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ bàbá sí àwọn òṣèré bí i, Kúnlé Afọláyan, Gabriel Afọláyan, Mojí Afọláyan àti Aremu Afọláyan.Afọláyan darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ tíátà tí Musa Ọláìyá, ní ọdún 1971, ó fi í sílẹ̀ láti dá ẹgbẹ́ tirẹ̀ sílẹ̀ lábala eré aláwàdà.Àtòjọ Díẹ̀ lára àwọn eré rẹ̀ Taxi Driver (1983) Àjàní ogún 1976)Àwọn ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1940àwọn ọjọ́aláìsí ní 1996àwọn òṣèré ará Nàìjíríààwọn òṣèré YORÙ Omo YORÙyo ka kúkúrú..
wikipedia
yo
(February 29, 1936 – July 18, 2015) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Calvin Coolidge "Calcal wortDádì (November 27, 1920 - September 8, 2013) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Estelle Nussbaum (April 4, 1928) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Donald McKinley Glover (September 25, 1983) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Catherine “Cathy” Weṣèlú (August 21, 1970) jẹ́ òṣèré ara Canada.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
AshJohn Adele .. (March 31, 1983) je osere ara Kánádà.Àwọn Ìtọ́kasíàwọn oṣere fíú ara Kánádà..
wikipedia
yo
Andrea Eva LILIman (July 19, 1984) jẹ́ òṣèré ará Kanadáàwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Kánádà..
wikipedia
yo
Germain (August 11, 1976) je osere ara Kánádà.Àwọn itọkasiàwọn oṣere poú ara Kánádà..
wikipedia
yo
Madeleine Marie Peters (March 30, 1996) jẹ́ òṣèré ará Kánádà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Kánádà..
wikipedia
yo
KurTis Eugene Warner (June 22, 1971) ...Àwọn ìtọ́kasíÀwọn elere-idaraya ara Amerika..
wikipedia
yo
Claire Margaret CorLett (July 9, 1999) jẹ́ òṣèré ará Canada.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
William Mills "Bill" IRWIN (April 11, 1950) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà..
wikipedia
yo
Mọ̀mọ́kọ́ Kochi jẹ́ òṣèré fíú àti atọ́kùn fíú ara Japan.Àwọn Ìtọ́kasí..
wikipedia
yo
Leonard Norman Cohen (Ọjọ́ìbí Oṣù Kẹ̀sán 21, 1934 – Oṣù Kọkànlá 7, 2016) jẹ́ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Kánádà.Àwọn òṣèré ara Amélwọ́n akọrin ará Kánádà..
wikipedia
yo
Oru ebi ebi( manga ati TV ọba Japan, nipa Risa ito ní 1990.Ìtọ́kasí OruChuban Ẹ̀bi (Manga) OruChuban Ẹ̀bi11 (TV) Manganímẹ..
wikipedia
yo
Olùdára Reka jẹ́ àtijọ́ iṣẹ́ ìlú kan ní apá Ariwa Fránsì, nítòsí ìlú Tourco àti àwọn àrí pẹ̀lú Bẹ́ljí..
wikipedia
yo
Agbegbe naa tobi to 13.23km, ti awon eniyan inu rẹ si je je nigba ikaniyan odun 2013.Àwọn itọkasi oju oju-opo wẹẹbu ìrìn-ajo afẹ̀ka afero ti
wikipedia
yo
coyqueque je ilu kan ni tsile.Awon ilu ati Abule ni tsile..
wikipedia
yo
Tourco () jẹ́ ìlú kan ní apá àríwá Fránsì, nítòsí ìlú USuscron nílé Bẹ́ljíọ̀m àti ìlú Roubaix..
wikipedia
yo
Agbegbe naa tobi to 15.19km, ti àwọn ènìyàn inú rẹ si jẹ ní nígbà ikaniyan ọdún 2013.Àwọn ìtọ́kasí ojú-opo wẹẹbu-opo wẹẹbu ìrìn-ajo afẹ̀ne tourco",
wikipedia
yo
Marseille () jẹ́ ìlú ebute ìgbàanì, èyí tá a dá nǹkan bíi 600 ṣááju Sànmánì Tiwa, ní apá gúúsù-ìlàoòrùn Fránsì..
wikipedia
yo
Agbegbe naa tobi to 240.62km ti àwọn ènìyàn ènìyàn inú rẹ̀ sì jẹ nígbà ikaniyan ọdún 2013.Àwọn ìtọ́kasí ojú ojú-opo wẹẹbu wẹẹbu ìrìn-ajo afẹ́ afẹ́ Marseille..
wikipedia
yo
ìdábàpò jẹ́ ìlú kan ni tsílé.Àwọn ìlú àti abúlé nì tsílẹ̀..
wikipedia
yo
Baskin-Robbins a jara yinyin ikun soobu ti o je agbaye ni iseda, burt BASkin ni ati Irv Robbins da ni 1953..
wikipedia
yo
Àwọn ilẹ̀-jẹ́ kan pataki ibití ó ti jùlọ ninu àwọn ayé pẹlu yìnyín ìpara ibi ti 5,800, 2,800 tí èyí tí ẹ̀ka wa wà ní United States tóbi..
wikipedia
yo
baskin Robbins ni ó ní yìnyín ìpara pinpin ní díẹ̀ ẹ síi ju 30 àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé..
wikipedia
yo
Awon ile-ti wa ni olu ni canton, Massachusetts.Ita ìjápọ BASkin-Robìhò osise aayedun 'bura$
wikipedia
yo
Moji ṣìpẹ̀ (Bii ni ọjọ ketadinlogbon oṣu keji ọdun 1975 - ojoketa osu karun-un odun 2017) je elere ori-itage Yorùbá ọmọ orile-ede Naijiria.Iṣẹ rẹ Moji je omo Victor Ọláìyá gbaju-gbaja ọ̀kọrin Highlife ile Naijiria..
wikipedia
yo
Mojí ìfibú bẹ̀rẹ̀ eré orí-ìtàgé rẹ̀ pẹ̀lú ilé iṣẹ́ wálé Adénúbò Super Story..
wikipedia
yo
O kopa to laami laaka ninu àwọn oṣere Nollywood Yorùbá ati Gẹẹsi lapapọ..
wikipedia
yo
Moji di gbajugbaja osere sinima agbelewo laarin awon akegbe re to ku latari ipa re to ko ninu ere Geesi ti a mo si no Pains no gains, ni eyi ti o ti kopa gege bi ireti, Sade Blade (2005), nkan Adùn (2008) ati ọmọ iya meta leyí (2009)..
wikipedia
yo
Moji yi pada lati esin Kìrìstẹ́nì si ẹ̀sin Islam ni ọdun 2014 fúnra rẹ̀.Ó kú ní Ọjọ́-kẹtàdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 2017, látàrí àìsàn ọkàn ní ìlú Canada, lẹ́yìn oṣù méjì tí ó bímọ kejì.Kí Ọlọ́run ò báwa fọ̀run ke..
wikipedia
yo
Ó dìgbà ó di gbére.Àwọn eré tí ó ti kópa ajé nílẹ̀ Olókun Ògbẹ̀ń ayé Àpáàdì ọmọ ìyá mẹ́ta Lèyí (2009) Nkan Adùn (2008) Sade Blade (2005)àwọn ìtọ́ni..
wikipedia
yo
Tajudeen Abọ́bi Adéwù jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà onílà àti olósèlú..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ Commission for Africa, ó sì jẹ́ olùdásílẹ̀ àti Alága Fate Foundation.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn ènìyàn àAlààyèàwọn ọmọ Ọmọbàáyoyo kukuruàwọn onírúsí ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
Tijani Babatunde Folawiyo (ti a tun mọ ni Tunde Folawiyo ) je onisowo omo orile-ede Naijiria..
wikipedia
yo
Oun ni Oludari Isakoso Ẹgbẹ Yinka Folawiyogẹgẹbi Forbes, o ni iye ti o ni ifoju ti $ 650 milionu.iṣẹ Tunde Folawiyo ni Alaga ti ẹgbẹ Yinka Folawiyo, agbari kan pẹlu awọn ifẹ si agbara, Iṣẹ-ogbin, gbigbe ọkọ, ati ohun-ini gidi..
wikipedia
yo
Igbimọ ajọṣepọ kan ti baba rẹ, Wahab Folawiyo da silẹ, Tunde gba Igbimọ ni ọdun 2008 nigbati baba se alaisi..
wikipedia
yo
O tun wa bi oludari ti MTN Nigeria Ltd, oludari alaṣẹ ti Yinka Folawiyo Group of Companies..
wikipedia
yo
Tunde tun da Folawiyo Energy Ltd silẹ, ẹka kan ti Yinka Folawiyo Group of Companies.Tunde jẹ oludari ti kii se adari ti access Bank PLC (access Bank Nigeria tẹlẹ) lati Oṣu Kẹwa Ọjọ 11 Oṣu Kẹwa Ọdun 2005 si Oṣu Kini Ọjọ 29, Ọdun 2014..
wikipedia
yo
O pe si Bar ti England ati Wales ni ọdun 1985, nibiti o ti bẹrẹ ilana ofin rẹ ni Nigeria pẹlu ile-iṣẹ Ogunsanya, ṣugbọn o fi ofin silẹ ni ọdun 1989..
wikipedia
yo
Lati ọdun 1996, Tunde tun ti ṣiṣẹ gẹgẹbi Igbakeji Alakoso ti Association ti Awọn Aṣoju & Awọn iṣelọpọ Ilu abinibi ti Nigeria (NAIPEC)..
wikipedia
yo
Lọwọlọwọ o jẹ Alaga ti Enyo Retail, Ile-iṣẹ Epo ati gaaṣi ti isalẹ ti Naijiria, ati Alaga ti Coronation Merchant Bank; Ile-ifowopamọ idoko-owo ni Nigeria.Eko Tunde Folawiyo lọ si Ile -iwe ti Iṣowo ti London, nibi ti o ti gba oye B.Sc ni Iṣowo ni 1980, ati LL B ni ọdun 1984..
wikipedia
yo
O gba ll M degree lati ile- eko giga Yunifasiti ti London ni osu karun ojo 1985.Awon Ola ni odun 2010, Tunde ni olugba aami eye olori ile Afirika..
wikipedia
yo
O si tun gba oye ninu iṣakoso Iṣowo lati Ile-ẹkọ giga Crescent ni Abeokuta, Nigeria.Tunde ṣe iranṣẹ bi Ambassador Iwurere, Ilu Ọ̀làjú ti Ilu ti Houston ati Ọlá Consul ti Barbados .Awọn Igbimọ ati Awọn Igbimọ Tunde jẹ ọmọ ẹgbẹ ti Igbimọ imọran Agbaye ti Ile -ẹkọ Alakoso Olori Afirika, Ile-iṣẹ Pan-Afirika ti a ṣe Igbẹhin fun idagbasoke ati àìgbo awọn iran tuntun ti Awọn oludari Afirika..
wikipedia
yo
Tunde jẹ ẹlẹgbẹ ti Duke ti Edinburgh's World Fellowship..
wikipedia
yo
O tun jẹ ọmọ ẹgbẹ ti Igbimọ Alakoso ti Yunifasiti Ipinle Eko ati Ijọba Ipinle Eko..
wikipedia
yo
O tun joko lori Igbimọ Awọn Alakoso ti Ile-ẹkọ giga Crescent ni Abeokuta.Awon itọkasi awọn Ọjọ́ìbí ni 1960awon eniyan Alààyè..
wikipedia
yo
Dr Oluranti Adebule, (bíi ní Ọjọ́nilelogbo Oṣù Kọkànlá Ọdún 1970) jẹ́ Ẹkẹẹdogun igbákejì Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó.Àwọn Ìtọ́kasí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1970àwọn ènìyàn Alààyèàyọkà Ekurù ṣòwò ará Nàìjíríà..
wikipedia
yo
George ADEdù Oguntade (CFR, CON) (A bi ni ojo kewa, osu keta odun, 1940), je adajo agba ti o ti feyinti ni ile-ẹjọ gigajulo ile Naijiria Supreme Court of Nigeria laarin May 19, 2004 si May 10, 2010.Awon itọkasi awon eniyan Alààyèawon omo YORÙyoka kukuruawon Ọjọ́ìbí ni 1940awon eniyan Alààyè
wikipedia
yo
Sonya Spence jẹ́ akọrin, olórin ìfẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Jamaica..
wikipedia
yo
Lara awon orin ti o ko ti o parun ni Jeer plane, in the Dark ati Let Love gígùn on.Awon itọkasiÀyọkà kukuru..
wikipedia
yo
ADEADE Kazeem AdeAde (A bi ní May 7, 1969) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà òṣìṣẹ́ ilé ìfowópamọ́..
wikipedia
yo
O tun jẹ oluṣakoso ati oludari ile ifowopamo first bank of Nigeria limited, ati gbogbo ẹka rẹ̀, o bo ipo yi lati ipo ti o wà tẹlẹ gẹgẹ bi group Chief Financial Officer..
wikipedia
yo
Ni 1994, lẹhin eyi ti o sise pelu Kpmg Professional Services, Citibank Nigeria, ati awon Africa Finance Corporation (AFC) ṣaaju ki o to darapọ mọ Firstbank ni oṣu Keje ọdun 2014.Awon itọkasi awọn eniyan Alààyèawon omo YORÙyo kukuruawon Ọjọ́ìbí ni 1969..
wikipedia
yo
Kemi Adeosun (a bi ni 9 March 1967) je omo orile ede Naijiria, o si tun je Minisita fun eto Iṣuna orile-ede Naijiria lati ojo Kọkànlá, osu Kọkànlá odun 2015.igbesi-aye reabi Kemi Adeosun si idile Ọgbẹni Adeosun ni odun 1967 si ilu London, ti awon obi rẹ je Ọmọ-bibi Ipinle Ogun ni orile ede Naijiria..
wikipedia
yo
O kẹkọọ gboye ninu imọ ijinle isuna Economics lati Ile-ẹkọ Fasiti ti Ilu London, ìyẹn University of East London ati ẹkọ diploma ninu imo ìfẹ̀tọ́ si isuna Awujọ iyen (Public Financial Management) ni Yunifasiti London.Ọmọ Kemi ti bẹrẹ iṣẹ rẹ bi oluranlowo iṣiro-owo ni British telecom, Lọndọnu, lati 1989 titi di ọdun 1990, lẹhin eyi o gbe lọ si Goodman Jones, London, ti n sise bi oṣiṣẹ oye ti oye lati ọdun 1990 titi di ọdun 1993.O di oluṣakoso Internal AuD8C Ilu London ati ijumọ prism lati 1994 titi di 2000 ṣaaju darapọ mọ Pricehouserun] Ilu Lọndọnu gẹgẹ bi Alakoso Alakoso lati ọdun 2000 si 2002..
wikipedia
yo
Ni ọdun 2002, Kemi di oludari owo ni Chapel Hill denham Management ati lẹhinna, oludari alakoso ni 2010..
wikipedia
yo
Lẹhin ti o n ṣiṣẹ pẹlu ajọṣepọ quo Vadis gẹgẹbi oludari alakoso lati ọdun 2010 si 2011, o ti yan Komisona fun Iṣuna ti Ipinle Ogun ni ọdun 2011.Kemi ṣètọ́jú ipa yii lati ọdun 2011 si ọdun 2015..
wikipedia
yo
O jẹ apakan pataki ti iṣẹ Ibikunle Ibikunle Amosun lati ko, eyiti o yi pada awon anfani eto-aje ti Ilu.Oṣù Kọkànlá ọdun 2015, ni a yan Adeosun Kemi ni Minisita fun Iṣuna Ilu Naijiria nipasẹ Alakoso Muhammadu Buhari..
wikipedia
yo
[1] Oroko iwe-ẹri NYSC ni ojo 7 keje odun 2018, irohin ori ayelujara ti Naijiria Premium Times tako esun pe Adeosun ti gba ofin ni gbẹ́nà ìmúkúrò NYSC re lati gba ọfiisi gbangba.Ni ojo 9 osu keje, oludari NYSC ti awon oniroyin ati ìbáṣepọ̀ gbogbo eniyan, Adeyemi Adenike tu alaye kan ti o jẹrisi pe Adeosun ni Ofin mu ibeere kan fun iwe-ẹri idasile, sugbon tun ṣalaye pe awon iwadii tun n tẹsiwaju lati jẹrisi itẹwọgba iwe-ẹri imukuro naa.Ni osu Kesan ojo 14 2018, Adeosun fi ipo sile gege bi Minisita fun Iṣuna ninu Lẹta kiko si Alakoso nitori esun ti o je Bakan Iroko NYSC ti o sọ.Ref>>>> on 14 September 2018, Adeosun resigned as Minister of Finance in a written to the President due due to the alleged NYSC for downloads for eni.egbe oselu ti ko se ose lu ninu gbogbo ise rẹ, Kemi Adeosun dara mo ẹgbẹ ijoba ti Naijiria, All Progressives Congress (APC) ni 5 May 2018.Awon itọkasi awọn eniyan Ape omo YORÙ Kakoko kukuru ni 1967 ni 1967..
wikipedia
yo
Olutayo Aderinokun (May 8, 1955 – June 14, 2011) je omo orile edeNaijiria onisowo onisowo, ti o si tun je oludari ile ifowopamo Guaranty Bank titi di ojo ti o fi okan..O si..O si je okan lara awon ti o ti gba ami eye ìdálọ́lá member of the Federal Republic, okan lara ami eye ti ijoba orile ede Naijiria ma n fi da awon eniyan Jankande lola.Awon itọkasi <reflist:àwọn omo YORÙbaa Schyo kukuruawon onisowo ara Nàìese Ọjọ́ìbí ni 1955awon ojo ni 2011..
wikipedia
yo
Adébọ́lá Ismail Akin (ti a bí ní oṣù Kọkànlá ọjọ́ karùn-din-lọ́gbọ̀n, ọdún 1963) ni Ìbàdàn, Ilu Ọyọ jẹ òǹtajà, Onimọ̀ràn Iṣowo ati Onínúure..
wikipedia
yo
O jẹ oludari alakoso egbe ti Courteville Business Solutions, Olupese ti Imọ-ẹrọ alaye ati awọn iṣẹ ijade ilana iṣowo..
wikipedia
yo
O je omo egbe ti igbimo awon Kuti ti East Africa Business Network (EAB)..
wikipedia
yo
O wa ni idanimọ gege bi ọkan ninu awon eniyan "Ọkàn-le-logun to wa ni oke ere wọn", nipasẹ iwe iroyin African Business Central Magazine.ibẹrẹpẹpẹ rẹ rẹ ati Eko ojo karun-din-lọgbọn osu kọkanla, ọdun 1963 ni won bi Bola Akindele ni iluIbadan, Ipinle Oyo..
wikipedia
yo
Ó dàgbà ní Èkó, ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga Ansar-Ud-deen, ní Isolo, ní Èkó láti ọdún 1974 sí ọdún 1979..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ ọmọ ilé ìwé gíga Faṣiti Obafemi Awolowo, Ile-Ife níbi tí ó ti gboyè pẹlu Bachelor of Arts ni iṣẹ́ àgbẹ̀..
wikipedia
yo
O gba oye "Masters" ni Banking & Finance lati Fasiti ilu Eko ti a n pe ni "University of Lagos" ni ọdun 1993 ati pe o tun gba oye doctorate of Business Administration (DBA) lati International School of Management, Paris..
wikipedia
yo
O tun jẹ ọmọ to jade lati ile-iwe Iṣowo Ilu London (London Business School) ati ile-iwe Iṣowo Ilu Eko (Lagos Business School.)aye rẹ gangan Bola Akindele ni awon oye ibile gege bi Oloye ọ̀túnba táyéṣe ti ile ògìjo ni Ipinle Eko, ati ti ọ̀túnba Bóbáṣèlú ti Ile Ejirin ni Epe, ni Eko..
wikipedia
yo
Wọ́n fún un ní oyè Islam ti Balógun Aaniní tí Ọlọ́run gbébẹ̀ Central Mosque ní Muṣin ní Ìpínlẹ̀ Èkó.Ó ṣe ìgbéyàwó sí Olabisi Sidiquat Akindele..
wikipedia
yo
Wọ́n ní ọmọ mẹrin, wọ́n sì jẹ́ ara ẹgbẹ́ Ikoyi Club ní Èkó.Àwọn ìtọ́ka si..
wikipedia
yo
Sarah Alade jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó jẹ́ adelé Gómìnà Central Bank of Nigeria, ní àsìkò tí Lamido Sanusi wà ní ìdádúró kí sáà rẹ̀ ó tó parí…
wikipedia
yo
Olori orile-ede Naijiria nigba naa, President Goodluck Jonathan ni o yan ni 20 February 2014..
wikipedia
yo
A yan Alade gẹ́gẹ́ bí adelé Gómìnà Central Bank of Nigeria lati 20 February 2014 titi ti a fi pada yan Godwin Emefiele gẹ́gẹ́ bi Gómìnà Ile ifowopamọ naa..
wikipedia
yo
Ṣaaju akoko yi, o ti wa bi Igbakeji Gomina (Economic Policy), Central Bank of Nigeria lati 26 March 2007Àwọn ìtọ́kasí àwọn eni ìAlààyèàwọn ọmọ YORÙbaa kukuruka..
wikipedia
yo
Ibukun Abiodun Awosika (tí wọ́n bí ní Bilderick Abiodun Motúnra ọmọbọ́lánlé Adekola Adekola ní 24, oṣù Kọkànlá 1962) je obinrin onisowo Naijiria, abani-soro ati onkowe..
wikipedia
yo
Ó jẹ́ alága tẹ́lẹ̀rí First Bank of Nigeria.Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí-ayé àti ẹ̀kọ́wọn bí í gẹ́gẹ́ bi í ọmọ kẹta nínú ọmọ méje ní Ìbàdàn, olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Oyo, ìkunkun parí ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti Èkó gíga ní St..
wikipedia
yo
Paul’s African Church Primary School, Èkó àti Methodist Girls' High School, Yábàá Kọ̀rúndún kí ó tó tẹ̀síwájú sí Yunifásítì Ifẹ̀(tí a mọ̀ ní Báyìí sí Yunifásítì Obáfẹ́mi Awólọ́wọ̀) níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ jáde pẹ̀lú BSc nínú Chemistry bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Architecture ni ó ti fẹ́ kọ́kọ́ kẹ́kọ̀ọ́ nípa rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀, ó sì tún ṣe àwọn kíko tí ó yàn nínú Accounting..
wikipedia
yo
O ni awon iwe eri post graduate ati mba leyin ti o pari opolopo awon eko idokowo ni Lagos Business School ati iese Business School - University of Navarra.Nigba ti o n se o-pọn-dandan odun-kan National Youth Service Corps Ìsìnlu (NYSC) ni Ipinle Kano, Ibukun Awosika sise gege bi i akose AuOi ni Akintola Williams & Co ti o pada di olùgbàlàte, sugbon pada leyin leyin naa si dara po mo dara mo Ali Nigeria., ile Migi., gege bi i a a Red-ifihan..
wikipedia
yo
Nínú ìpa rẹ̀ láti dá dúró, ó dá ilé-iṣẹ́ tí í ṣẹ̀dá Furníture tí ó pè ní àgùs ní ní 1989 kí ó tó yí yí padà sí The Chair Centre Limited àti Sokoa Chair Centre Limited lẹ́yìn náà lẹ́yìn níkàn níkànpẹ̀lú pẹ̀lúa Ṣ.A àti Guaranty Trust Bank in 2004.O jẹ́ ọ̀kan lára African Leadership fún òṣìṣẹ́ àti aṣuma Global Leadership Network, Ibukun Awosika jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Summit Summit Group, ọ̀kan lára Àjọ ní Sovere ní Ṣeusi Fund àti alága, Àjọ gbé lé ìdùn ohun Women, Business ní Business Service Service.. Business Service..
wikipedia
yo