cleaned_text
stringlengths 6
2.09k
| source
stringclasses 2
values | language
stringclasses 1
value |
---|---|---|
Inu ile eko Markaz laarin osere awon ile eko esin Islam to ku ni won ti koko seto ilana ikoni ti o se àdáyanrí bi won yoo se pin awon omo si iyara ikekoo to ye.. | wikipedia | yo |
Bakan naa ninu Markaz ni awon omo akekoo esin Islam ati eko Larubawa ti koko wo aṣọ idanimo ile-eko (Schoo uniform), ti won si n jókòó lori aga ti won si tun kowe lori tabili dipo ori eni tabi ile lasan ti won si n lo gege ìkọ̀wé ati iwe pelu.. | wikipedia | yo |
Ẹ̀wẹ̀, Markaz naa ni won ti koko bere ilana idanwo eko fun awon akekoo lori ohun ti won ti ko won lati le fi se Akande(Assessment) , ati lati se igbega tabi lati fidi eni ti o ba padanu remi.. | wikipedia | yo |
Bakan naa ni won tun ṣàgbékalẹ̀ iwe ẹ̀rí to yanranti fún àwọn tó bá keko jade nile eko naa.. | wikipedia | yo |
Leyin ti won ba ti eko jade tan, won yoo si tun pada silu won lati da irufe ile-eko bi ti Markaz kale si ilu won labe ase ile-eko Markaz Agege ati lati maa se Afaa won lo.Awon itọka si.. | wikipedia | yo |
Sir Sina Peters tí wọ́n bí ní ọjọ́ àkítà Oṣù kẹta, ọdún 1958 (30 May 1958) ní ó jẹ́ olórin Jùjú ọmọ ilẹ̀ Nàíjíríàrí ayé.Ìgbésí rẹ̀ wọ́n bí olúwa Akanbi Peters ní ìpínlè Ògùn.. | wikipedia | yo |
Peters bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ láti ìgbà èwe rẹ̀, nígbà tí ó mà ń ṣeré pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́gbẹ́ rẹ̀ lábẹ́ orúkọ “ Olúṣínà àti àwọn ọmọ ìyá-méjìlá gidi (OlùShina and His Twelve Fantastic Brothers).. | wikipedia | yo |
Lásìkò náà, ni ó ti kọ́ bí wọ́n ṣe ń ta dùrù (Piano) tí ó sì padà di ọmọ lẹ́yìn Ebenezer Obey.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn èyí, ó kúrò lẹ́yìn Obey láti dara pọ̀ mọ́ ọmọ ẹgbẹ́ ọ̀gbẹ́ni General Prince Adékúnlé gẹ́gẹ́ bi Oni jì.. | wikipedia | yo |
Nígbà míràn tí ó àárẹ̀ bá kọlu ọ̀gbẹ́ Adékúnlé, Peters ló ma ń sábà ṣíwájú orin fún ẹgbẹ́ náà.. | wikipedia | yo |
Láti ni ó kúrò lẹ́yìn Adékúnlé lati dá ẹgbẹ́ Sina Adewale sílẹ̀ pẹ̀lú ìlú-mooka olórin Jùjú ṣẹgun Adewale.. | wikipedia | yo |
Àmọ́ sá, kò pé tí wọ́n tún fi pínpin lẹ́yìn tí ó ti ṣe àwọn àwo orin ele-ò-kan jáde pẹ̀lú Segun Adéwe láàrín ọdún 1980, ní ó pinu láti dá ẹgbẹ́ òṣèré tire kalẹ̀ tí ó pè ní ní "Sir Shina Peters & His International Stars". Peters ló tún jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé nínú eré 'agbára owó (Money Power).. Power | wikipedia | yo |
Àfi eré yìí tí Ola Balogun jẹ́ olùwà rẹ̀ ni ó ti yófẹ̀ẹ́ pẹ̀lú arabinrin Clastanon Chukwura tí òun náà jẹ́ òṣèré tí wọ́n sì jọ di tọkọ-táyé tí wọ́n sì bí ọmọ ọkùnrin kan funrà wọn, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Clarence Peters.iṣẹ́ orin rẹ̀ ẹgbẹ́ sir Shina Peters & His International Stars gbé àwo orin 'Ace (Afro-Jùjú series series 1) jáde ní ọdún 1989.. | wikipedia | yo |
Àwo orin tí ó jáde lábẹ́ CBS Records of Nigeria ni ó sọ Peters di gbajú-gbajà olórin. "Ace" tí olú Akins bá gbé jáde ní ó jẹ́ àkójọpọ̀ Jùjú àti Afró (Afro).. | wikipedia | yo |
Awo orin ti o so ẹya, Ede, ati asa ile Naijiria papo.. | wikipedia | yo |
Orin Afro Jùjú ni ó jẹ́ orin ti ọ̀wọ́ ìlú àti ijó rẹ̀ le látàrí àkójọpọ̀ ẹ̀rọ (Electronic keyboards, Sayínding àti Guita).. | wikipedia | yo |
Ọ̀pọ́lọpọ̀ orin inú àwo náà pàá pàá àjọ ‘ijó’ ni àwọn ènìyàn fẹ́ràn jù lọ.. | wikipedia | yo |
Àwo orin 'Shinamania (Afro-Juju series 2) * ni ó fese re mule wípé ẹgbẹ́ 'sir Shina Peters & His International Stars' ti ṣe tan lati so ere Jùjú di otun ni awujo orin Ilẹ̀ Adúláwọ̀.. | wikipedia | yo |
Pẹ̀lú àṣeyọrí sir Shina Peters yí ni ó fi hàn wípé òun ni olùdásílẹ̀ ẹ̀yà orin eré (Afro Jùjú) tí ó dá dúró títí di òní. Àwo orin mẹ́rìndín-lógún (16 album) ni ó ti gbé jáde.sir Shina Peters, tí wọ́n tún ń dápé ní "SS", ni ó ti gba oríṣiríṣi àmì-ẹ̀yẹ ìdánimọ̀ fún ìgbìyànjú rẹ̀ lórí iṣẹ́ ọnà àtinúdá rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Shina Peters & His International Stars ti di igi àlọ́yè láàrín àwùjọ orin àgbáyé.. | wikipedia | yo |
Wọ́n gba sir Shina Peters láyè sí US tour to Orbit entertainment in 2012, láti ma kó àwọn ènìyàn rin ìrìn-ajo kaa kiri ilẹ̀ Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
SSp ni ó fi ìlú Èkó ṣe ibùgbé, tí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ sì lágbára síbẹ̀ láwùjọ orin ilẹ̀ Nàíjíríà.Awon àwo orin rẹ̀ Way to Freedom (1980) Freedom (1981) Money Power * (1982) kọ́ temi fún mi (1984) Sewẹ̀yìn (1986) Ace "Afro Jùjú series series (1989) Shinamania (1990) Dancing time (1991) Experience (1992) Mr.. | wikipedia | yo |
President (1993) My Child (1994) Olode (1995) Love (1996) Réunion (1997) Play (1999) Happy Hour (2001) Pay Back Time (2005) SṢàṣà (2006) D One 4 Me (2012)References Àwọn Ọjọ́ìbí ní 1958Àwọn Ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Antwan Wiggins tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Kẹ́ta ọdún 1980 ( March 6, 1980) ní ìlú Brooklyn.. | wikipedia | yo |
Je ọ̀kọ̀rin hip hop ọmọ orile ede Amẹrika. Oruko ti won mọ̀ọ́ pelu re ni 'Awonhen | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2014, ó dá ilé- iṣẹ́ orin “Don't Sleep" kalẹ̀ pẹ̀lú àjọṣepọ̀ Phoniks.. | wikipedia | yo |
Sade jẹ́ abúlé kan ní ìlú Karmálà taluka tí Solapur District ní ìpínlẹ̀ Maharashtra, ilẹ̀ India.Tìbú tọ́rọ̀ rẹ̀ Ṣadé tó ìwọ̀n ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àti igba àti mẹ́rìndín-láàdọ́rin ( tí ó sì ní ilé ìgbẹ́ tí ó tó 1077 lásìkò ìkànìyàn tí ó wáyé ní ọdún 2011 (2011 Census of India).. | wikipedia | yo |
Àwọn ọkùnrin ibẹ̀ tó 2315, tí àwọn obìnrin ibẹ̀ sì tó 2261, tí àkójọpọ̀ àwọn ọmọdé láti ọdún mẹ́fà wálẹ̀ jẹ́ 493.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Adeniran Ogunsanya College of Education, tí àgékúrú rẹ̀ ń jẹ́ (AOCOED), jẹ́ ilé-ẹ̀kó gíga (Higher Education) tí ó wà ní ìlú Ọ̀tọ̀-Àwórì lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Ọ̀jọ́, Ìpínlẹ̀ Èkó.. | wikipedia | yo |
Ile- eko Adeniran Ogunsanya n ṣeto imo ikoni gege bi oluko ti o si n pese iwe eri 'Nigeria Certificate in education' (nce) ati imo ìkọ́ni ti ile-eko agba Alakoko (undergraduate first degree), pèlú ìbásepo Ile-ẹkọ Agba ti Ipinle ( Ekiti State University )Ìtàn Ile-ẹkọ naa Ile-ẹkọ giga naa ti won koko n pe ni "Ile-ẹkọ giga ti Ipinle Eko" (Lagos State College of Education), ni won da sile ni odun 1958 gege bi ile-eko awon olukọ onípele keta, ti won si koko gba awon akekoo ti o to Àádọ́sàán (90) ní ọdún àkọ́kọ́.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1982, wọ́n gbé ilé-ẹ̀kọ́ náà kúrò ní Súrùlérè lọ sí Ọ̀tọ̀-Àwórì, látàrí àìtó àwọn ohun amáyé-dẹrùn ìgbà-lódé àti pípọ̀ tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń pọ̀ sí lọ́dọọdún.Lára àwọn lààmì-laaka tó ti jáde níbẹ̀ Kúnlé Kúnlé Àjàyí Sarah Adégi sọsàn sanàì o.. | wikipedia | yo |
Ọ̀tọ̀-Awori jẹ́ ìjoba ìdàgbà-sókè agbègbè ìjoba ìbílè Ọ̀jọ́, tí ó wà ní òpópónà márosẹ̀ Èkó sí Agbada-rigi.Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí ó wà níbẹ̀ Adéníran Ògúnsànyà College of Education National PostPost College of Nigeriae tún le wọ History of Lagos Awori District settlement ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Níyì Adéolókun tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹ́ta oṣù Kọkànlá ọdún 1990 ( 3 November 1990) jẹ́ agbá bọ́ọ̀lù Rugby fún (Irish Rugby Union).. | wikipedia | yo |
Adéolókun ló tún ń gbá rugby fún ikọ̀ ( Connacht) ní Pro14.. | wikipedia | yo |
Ó dára pọ̀ mọ́ Connacht ní ọdún 2014 láti ilé-ẹ̀kọ́ ‘Trinity Collegeará | wikipedia | yo |
Lásìkò tí ó fi wà pẹ̀lú ilé-ẹ̀kọ́ àgbà ti (Dublin University), ó gbá rugby sevens fún ikọ̀ ilé-ẹ̀kọ́ náà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ wọ́n bí Adéolókun ní ìlú Ìbàdàn,ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ó lọ sí ilẹ̀ Ireland pẹ̀lú àwọn òbí rẹ̀ ní ọdún 2001 nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mọ́kànlá (age 11).. | wikipedia | yo |
Ó gbá bọ́ọ̀lù afẹ̀ṣẹ́-Gbá fún Gaelic football àti Templeogue Synge Street tí ó sì tún gbá bọ́ọ̀lù fún League of Ireland àti Shel’s ti òjé-wẹ́wẹ́ tí ọjọ́ orí wọn kò ju ogún ọdún lọ (under 20).. | wikipedia | yo |
Ó kọ́kọ́ gbá fún rugby Union gẹ́gẹ́ bí akẹ́kọ́ ní De La Salle College ní Churchtown.Iṣẹ́ òòjọ́ rẹ̀ìgbà Ewe rẹ̀ Adéolókun gbá fún Leinster nígbà èwe rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Lẹ́yìn tí ó kúrò níbẹ̀, ó dara pọ̀ mọ́ ẹ̀gbẹ́ De La Salle tí ó jẹ́ ikọ̀ àgbà fún ilé-ẹ̀kọ́ náà.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 2009, All-Ireland League nílé ìwé Dublin University bá fìwé pèé lábẹ́ àṣẹ olùdarí bọ́ọ̀lù Rugby ìyẹn Tony Stálákàgbòde.. | wikipedia | yo |
Adéolókun gbá bọ́ọ̀lù yìí fún ikọ̀ náà fún ọdún mẹ́rin.. | wikipedia | yo |
Lásìkò tí ó wà níbẹ̀, ikọ̀ náà gba ife ẹyẹ ‘All-Ireland Championships' ní tẹ̀lé-n- tẹ̀lé ní ọdún 2011 àti 2012.Connacht ní oṣù Karùún ọdún 2014, wọ́n kéde rẹ̀ wípé Adeolokun fọwọ́ sí ìwé àdéhùn pẹ̀lú (Connacht) ìkọ́ rẹ̀ tí ó wà yìí tí ó jẹ́ ọlọ́dún kan.. | wikipedia | yo |
Olùkọ́ni Nigel Carolan ni ó tọ́ka rẹ̀ fún ilé-ẹ̀kọ́ náà, lẹ́yìn tí ó ti yege nínú ìdánwò rẹ̀ ní Connacht Eagles, ní oṣù kẹrin ọdún 2014.Adéolókun fakọyọ fún ikọ̀ rẹ̀ (Connacht) ní ọjọ́ kẹfà oṣù Kẹ́sà ọdún 2014, nígbà tí wọ́n gbá pẹ̀lú ikọ̀ Newport Gwent Dragons níbi ìfẹsẹ̀-wọnsẹ̀ ìṣíde òpin ọ̀sẹ̀ ní 2014-15 PRO12, níbi tí ó ti ṣe ìrànwọ́ fún akẹgbẹ́ rẹ̀ Eoin McKeon .. | wikipedia | yo |
O tun gba bọọlu akọkọ rẹ sinu awọn leyin ifowo bowe rẹ nigba ti won gba pelu iko La Rochelle nibi idije 2014-15 Rugby Challenge Cup.. | wikipedia | yo |
Gbogbo bọ́ọ̀lù tí ó gbá nínú ìdíje League jẹ́ mẹ́sàán ti ti Challenge Cup sì jẹ́ mẹ́rin nínú ìpele ìbẹ̀rẹ̀ ọdún. Ní Oṣù Kọkànlá Ọdún 2014, wọ́n kéde rẹ̀ wípé ó tún fọwọ́ bọ̀wé àdéhùn mìíràn pẹ̀lú ikọ̀ rẹ̀ yìí Connacht láti wà pẹ̀lú Ikọ̀ náà títí di òpin ọdún 2016-17.Ní 28 May 2016, (Connacht) gba ìfẹ́ ẹ̀yẹ àkọ́kọ́ irú rẹ̀ ní 2015-16 Pro12 lẹ́yìn tí wọ́n jáwé olúborí pẹ̀lú ayò 20 sí 10 tako Leinster níbi ìfẹ̀sẹ̀-wọnsẹ̀ tó kẹ́yìn ìdíje náà.. | wikipedia | yo |
Tí ìréjáde sì gba àmì ayo náà wọlé.Ireland, November, 2016 Adéolókun gba ìwé ẹka àkọ́kọ́ rẹ̀ lati dara pọ̀ mọ́ Ikọ̀ Agba bọ́ọ̀lù àgbà fún ilẹ̀ Ireland.. | wikipedia | yo |
Ó sì fakọ yọ nínú ikọ̀ náà ní ọjọ́ kejìlá oṣù kọkànlá ọdún 2016, nígbà tí wọ́n fi rọ́pò akẹgbẹ́ rẹ̀ Craig Gilroy tako ikọ̀ agbá rugby ilẹ̀ Canada.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1990àwọn ènìyàn Alààyè.. | wikipedia | yo |
Èyí ni àtòjọ àwọn olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Àwọn tí wọ́n jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká nìkan ni a kó jọ sí abẹ́ ààtò yí.. | wikipedia | yo |
Inúsá tìmí Dméjèèjì - olórin tí ó gba àmì ẹ̀yẹ ti idol West Africa (2007) Stella Damasus - olórin Sọ́ọ̀lù (soul) àti R&B Dammy Krane Darey - olórin R&B àti Olùkọrin Davido - olórin Pọ́ọ̀pù Yinka Davies - olórin Jáàsì Oliver Oliver De Coque Sa De Coque - olórin hip hop àti Ráàpù Dekumzy - olórin R&B àti Highlife Adi Adi Di'ja Tonto Dikeh - olórin Pọ́ọ̀pù Don Jazzy - olórin tí ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jade d'Prince - olórin Afro àti Pọ́ọ̀pù Dr.. | wikipedia | yo |
Ahabu Dr Sid - olórin Pọ́ọ̀pù Duncan Mighty - olórin Sciencelé Frank Edwards - Olórin Gospel Omotola Jalade Ekeinde - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù eldé - olórin Ráàpù, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde Emma Nyra - olórin R&B Emmy gẹ́ẹ́ - olórin Ráàpù Alhaji Dátá Epo-Àkàrà - Oalef Falz - olórin Ráàpù àti Olùkọrin Majek Fashek - olórin R&B àti Olùkọrinàti Olùkọrin Faze - olórin olórin R& FLAour N'aba - olórin Pọ́ọ̀pù àti Highlife ton Garye Gar - olórin R&B àti Olùkọrin Adekunle Gold - olórin àti Olùkọrin Gyanh GH Harrysong - olórin àti Olùkọrin Humble Humble - Afro àti Pọ́ọ̀pù Ice Prince - olórin Ráàpù Haruna Ishola Ishola - olórin pàlà Helen Parker-Jayne Isibor - olórin àti Olùkọrin Ìfẹ́rìndé Ọláese Oya - Pop singer j Jesse Jag - olórin Ráàpù Joe el Johnny edlle Tamara Jones - olórin R&B àti Olùkọrin K Hacée Kefèé Peter King Tunde King King Wmooth - olórin régè Ki Daniel Kóker Kódker Bello Ayin Ko Kollington Abiodun Mo bi ní (1980), Gospel Gospel, àti opera Fela Kuti - olórin Jáàsì, afrobeat, onílù àti Olùkọrin Femi Kuti - olórin Jaa, afrobeat, onílù àti Olùkọrin Seun Kuti - olórin Jaa, afrobeat, onílù àti Olùkọrin l àti onílù àti onílù lára George - olórin Gospel Rex Lawson Lil K K ; Lé M.I -i olórin Ráàpù M | wikipedia | yo |
Martin - olórin tí ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde May ven Prince Nico M[ Maud Meyer - olórin Loáàsì Jáàsì Mike Mipe Ẹ̀jẹ̀ - olórin Highlife Mo' Èkínní - Pọ́ọ̀pù Mode 9 - olórin Ráàpù Cynthia Morgan - olórin Pọ́ọ̀pù àti ọ̀pọ̀ kíní Bv Mr raw mú _*“ - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin - olórin Ráàpù Múra Ofèsì La ètò C Nathani 14 Tunde Nightingale Àlàga- Afro - Afro Ni - olórin Jáàsì àti sóòlù Genevieve Nnaji - olórin Pọ́ọ̀pù Nneka - olórin Pọ́ọ̀pù àti Sọ́ọ̀lù Nosa - olórin Gobùkùlo Godọ́gba Alhaji Abass Àkàndé - olórin Fújì Ebenezer Ebenezer- olórin Jùjú àti olórin - olórin R&B àti Gospel Dókítà O - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin Logo Aderó délẹ̀ Ọjọ́ - olórin Jùjú àti Olùkọrin Ọkọ̀- àti Kú Highlife àti Olùkọrin Olùma Okoye Same Sam - olórin Gospel Victor Ni Olóòtú - Yẹ - olórin Pọ́ọ̀pù àti Ráàpù Babátúndé Ọlátúnjí Yusuf - - olórin Àwó Àlàdọ́gba - olórin Sọ́ọ̀lù) Onyeka bak - olórin Pọ́ọ̀pù William Onyer Orezir - olórin régè Brothers Ori Femi Osita Osa Orlando Robert Owo Highlife Ọjọ́ Adé - olórin Gospel Oxlade Olù Ozokwor Ozokwor - Highlife Patoranking - Ara régè àti dancehall - Ráàpù Ráàpù, Pọ́ọ̀pù O tun Ó n gbé àwọn olórin mìíràn Mi Mi Peru - olórin Afro-Jùjú olórin Phy - olórin Ráàpù Ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn mìíràn Olù* | wikipedia | yo |
Ọjọ́ Adé ni wọ́n bí ní (ọjọ́ kẹwa, oṣù kẹwa ọdún 1959) , ó jẹ́ olórin, Olùkọ́ orin-èmi Osìpẹ̀eli àti Olùṣọ́ Àgùtàn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ wọ́n bí ni ọjọ́ kẹwàá oṣù Kẹwàá ọdún 1959 (October 10, 1959) ni ilú Ikeji-ilẹ̀, ilú nlá kan ni ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.O kẹkọ ni ilé-ẹ̀kọ́ St.. | wikipedia | yo |
Judge Anglican Church ti o wa ni ikeji-Ile ṣaaju ki o to dari lọ sílùú Eko fun ìkọsẹ̀ owo elerẹ̀un.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1987, ó tún tẹ̀ síwájú láti kẹ́kọ̀ọ́ ní Ilé-ẹ̀kọ́ Bíbélì (Calvary International Bible College) lábẹ́ àkóso Olùṣọ́ Àgùtàn Rev.. | wikipedia | yo |
Ailorin, tí ó n ṣiṣẹ́ àtẹ̀síwájú àti Ìhìn-rere ní ìlú Ìbàdàn .Iṣẹ́ òòjọ́ rẹ̀ ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ rẹ̀ ní ọdún 1977 nígbà tí ó dára pọ̀ mọ́ àwọn akọrin ijó, ṣùgbọ́n tí ó dá ẹgbẹ́ akọrin tirẹ̀ kalẹ̀ ní ọdún 1979.Ní ọdún 1981, tí ó jẹ́ ọdún méjì lẹ́yìn tí ó dá ẹgbẹ́ akọrin ẹ̀mí tirẹ̀ sílẹ̀, ó kọ orin ẹ̀mí kan jáde tí ó sọọ́ di ìlú-mọ̀ọ́ká tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ 'Jésù tọ Funmi''' , tí ó sì tún gbé òmíràn jáde tí ó tún pe àkọ́lé rẹ̀ ní Satani kọ sinmi’’ | wikipedia | yo |
Ó wà lára àwọn olórin ẹ̀mí ti ìlànà Kristẹ́nì tí ó ti lààmì-laaka ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà pẹ̀lú iṣẹ́ takun takun rẹ̀.Àwọn ìtọ́ka sí àwọn Ọjọ́ìbí ní 1959àwọn ènìyàn alààyè.. | wikipedia | yo |
Wọ́n bí Wasiu Alabi Pasuma ní (November 27, 1967) sí Mushin ní ìpínlẹ̀ Èkó, tí bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Kwara òun náà ni wọ́n tún n pè ní "Ọ̀gánlá.. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún yàán fún àmì ẹ̀yẹ 'olórin tí kìí ṣe olórin ẹ̀sìn Islam , tó kópa tó pọ̀ nínú àwo orin ẹ̀sìn Islam' ní ọdún 2016, òun pẹ̀lú King Saheed Òṣùpá, Sule Àlàó Malaika, Shefiu Àlàó, Taye Curki, àti múrí Thunder.Àwọn àwo orin rẹ̀ Alhaji Wasiu Alabi Pasuma ti gbé àwo orin Fújì tó lé ní ọgbọ̀n 30 jáde láti ọdún 1993 .. | wikipedia | yo |
Saheed Balogun ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kárùún oṣù kejì ọdún 1967 (February 5, 1967) ní ìpínlẹ̀ Kwara.. | wikipedia | yo |
Ó jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré jáde, adarí eré, àti olùṣe fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà.Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ rẹ̀ wọ́n bí Saheed ní Ìpínlẹ̀ Kwara tí ó jẹ́ (North Central Nigeria), ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Oyo.. | wikipedia | yo |
Nibi ti o ti kawe alakoo bẹrẹ , iwe girama ati ile iwe giga .. | wikipedia | yo |
Ó kàwé jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ 'Kwara State Polytechnic' tí wọ́n ti yí padà sí (Kwara State University).Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 1978, nígbà tí ó kọ́kọ́ ṣe ètò rẹ̀ kan lórí èrò amóhùn-máwòrán tí ó pè ní "Youth today" lórí NTA.. | wikipedia | yo |
Ó ṣe sinimá àgbéléwò rẹ̀ àkọ́kọ́ tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ 'City Girl''' ní ọdún 1989, amo tí ó sì ti gbé ọ̀pọ̀ sinimá jáde tí ó sì tún ti ṣe adarí fún ọ̀pọ̀ eré orí-ìtàgé mìíràn mìíràn.. | wikipedia | yo |
àwọn ẹbí rẹ̀ ó fẹ́ ìyàwó rẹ̀ tí òun náà jẹ́ òṣèré orí ìtàgé ìyẹn Fathia Balógun ṣùgbọ́n wọ́n ti pínyà báyìí.. | wikipedia | yo |
Kwara State Polytechnic jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ilé Nàíjíríà tí olórí ìjọba ìjọba ológun ìpínlẹ̀ Kwara tẹ́lẹ̀ Ọ̀gágun Col Col.. | wikipedia | yo |
David bámigboye da silẹ ni ọdun 1973 ni wọ́n kéde rẹ̀ lẹ́yìn tí wọ́n ti pinu lati da ile-ẹkọ naa silẹ si Ipinle Kwara lọ́dún 1971.. | wikipedia | yo |
Ile-eko naa lo wa ni Ilorin ti o je olu ilu ipinle naa.. | wikipedia | yo |
Ilé-ẹ̀kọ́ náà kọ́kọ́ gba àwọn ọgọ́rùún ó lé mẹ́wàá akẹ́kọ̀ọ́ wọlé nígbà àkọ́kọ́ fún sáà ètò ẹ̀kọ́ ọdún náà nígbà tí wọ́n ń pèsè ètò ẹ̀kọ́ National diploma àti Higher National diploma fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọn gbogbo.Ẹ tún le wo list of Polytechnics in níṣìíríawọn ìtọ́ka sí ìpínlẹ̀ KwaraYunifásítì ní Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Eléyìí ni àtòjọ àwọn olórin Highlife ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n gbajúmọ̀ jùlọ ní àtò à – Y.. | wikipedia | yo |
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ghana ni ọrini Highlife ti ṣe wà tí ó fi tàn dé gbogbo ilẹ̀ Adúláwọ̀ pàá pàá jùlọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.A Adekunle Gold Ambassador OsayOmore Josephb Bàbá Ken Okulòlò Bobby Benson Bright Chimezie Bola Johnsond Dr sir warriorf Fatai Rolling Dollar Fela Kuti Femi Kuti Fela Sowande flaour n'abania o Orlando Owoh Oliver de Coque Oriental Brothers Osita Osabe Prince Nico MBargar Rex Lawson Roy (1914 Gbígbàdúrà ṣeun Kuti Victor Ọláìni Victor Therewaw Wilber E.’E tun le wo àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Ghana ni ọrini Highlife ti ṣe wà tí ó fi tàn dé gbogbo ilẹ̀ Adúláwọ̀ pàá pàá jùlọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.A Adekunle Golda Ambassador Osay Josephb Bàbá Ken Okulòlò Bobby Benson Bright Chimezie Bola Johnsond Dr sir warriorf Fatai Rolling Dollar Fela Kuti Femi Kuti Fela Sowande flaour n'abania o Orlando Owoh Oliver de Coque Oriental Brothers Osita Osabe Osap Prince Nico Mgar Rex Lawson Roy Chicolùdarí ṣeun Kuti * Victor Ọláì Victor ùwaww Wilber E-E tun le wo àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Jennifer Sarah “Jenny” Sikute (March 25, 1982) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.Àwọn ìtọ́kasíàwọn òṣèré fíú ará Amẹ́ríkà.. | wikipedia | yo |
Deleda Òjó jẹ́ olórin Jùjú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ọ̀pọ̀ ènìyàn gbà wípé òun ni ó tan ẹ̀yà orin náà kálẹ̀.Iṣẹ́ orin rẹ̀ délẹ̀ ọjọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin rẹ̀ ní pẹrẹu nígbà tí ó ṣfu-pàdé olórin kan tí ó ń jẹ́ Victor Ọláìyá ẹni tí ó gba délé sí inú ọmọ ẹgbẹ́ akọrin rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Ní ọdún 1961, ọjọ́ dá ẹgbẹ́ òṣèré akọrin tirẹ̀ náà kalẹ̀ tí ó pè ní “Délé Òjó & His Star Brothers Brothers lẹ́yìn tí Ọláìyá tú ẹgbẹ́ akọrin tirẹ̀ ká .. | wikipedia | yo |
Bákan náà ni ó tún gbé orin rẹ̀ dé ọ̀pọ̀ ìpínlẹ̀ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà.Awo orin rẹ̀ aláfíà Jùjú Music at Its Bestáwọn ìtọ́ka sí àwọn ènìyàn alààyè.. | wikipedia | yo |
National Democratic Cox (NADECO) ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹẹ̀sílẹ̀ oṣù Kárùún ọdún 1994 (May 15, 1994) láti ọwọ́ (Broad Cophe of Nigerian àwọ̀nts), tí ó pe ìjọba ológun tí Sani Abacha lati kúrò lórí àléfà fún ẹni adibo òbòyàn June 12, 1993, ìyẹn M.. | wikipedia | yo |
Abiola.Àwọn afẹ̀họ́ han oloselu náà wá láti apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Wọ́n sì jẹ́ kí àwọn ènìyàn mọ ìdí tí wọ́n fi gbọ́dọ̀ fajúro sí ìṣèjọba ológun àsìkò náà.Ní June 11, 1994, nípa ìtẹ́lẹ̀ àlàkalẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú NADECO, Abiola kéde ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti ẹni tó jáwé olúborí nínú ìdìbò June 12, tí ó sì fara sóko lẹ́yìn tí ìjọba ológun sì fipá mú tì mọ́lẹ̀ ní June 23.Ní ọjọ́ kẹtàdín-lógún osù Kọkànlá ọdún 1994 (17 November 1994), Àdó olóró dùn gbámu ní pápákọ̀ Òfurufú Èkó ní Àyájọ́ Ayẹyẹ ọdún kan lórí àléfà Ọ̀gágun Sani Abasha.. | wikipedia | yo |
Àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ òṣèlú NADECO kìlọ̀ pé " Àjálù ni yóò jẹ́ fún gbogbo àgbáyé, bí àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà bá gbà wípé jàgídí-jàgan ló lè mú kí àwùjọ àgbáyé yé dá sọ̀rọ̀ náà.”Wálé Ọ̀ṣun, tí ó jẹ́ fìdí Hee wéwẹ́ Akọ̀wé (acting secretary-general) fún ẹgbẹ́ òṣèlú náà ni wọ́n fi sàháàẹ́ ní ọjọ́ kósọ́-lógún oṣù Karùún ọdún 1995 (May 19, 1995).. | wikipedia | yo |
Wọ́n tún fi pańpẹ́ Ọba mú Olóyè Cornelius Adébá lẹ́yìn oṣù kan tí àdó olóró kan tún dún ní ìlú ìlọrin àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ NADECO míràn.. | wikipedia | yo |
Ní July 1997, ìjọba ológun tún fẹ̀sùn kan ẹgbẹ́ NADECO wípé àwọn ni wọ́n wà nídì jíju àdó olóró oríṣiríṣi ibùdó àwọn ológun tó ti wáyé , tí ó sì tún sọ ní gbangba wípé àwọn agbọ̀rọ̀dùn ilẹ̀ Amẹ́ríkà kan náà sì tún kún wọn lọ́wọ́ lórí ìwà láabi náà.. | wikipedia | yo |
Ẹni tí ó jẹ́ ọ̀gá àwọn ọlọ́pàá tẹ́lẹ̀, Ibrahim Coomassie, sọ wípé òun fẹ́ fi ọ̀rọ̀ wá aṣojú ilẹ̀ Amẹ́ríkà sí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ lẹ́nu wò .ní August 1999, ẹgbẹ́ òṣèlú náà pé Ọ̀gágun Sani Abasha lẹ́jọ́ lórí ẹ̀sùn wípé kò wá san owó ìtanràn tí ó tó $20 million fún ìwà ìrẹ́jẹ rẹ̀ lórí ẹgbẹ́ náà, lásìkò ìṣèjọba rẹ̀.Àwọn ìtọ́ka sí.. | wikipedia | yo |
Èyí ni àtòjọ àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà.Àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ìgbà ìjọba ẹlẹ́kẹrin láti 1999 títí di oní (1999-present) ìṣí Nigeria Renehán Party (AN) Advanced Congress of “ Democrats (AC) Alliance for Democracy (AD) Alliance for New Nigeria (Ann) Action Democratic Party (ADP) All Democratic Peoples Movement (AD) All Progressives Congress (APC) African Democratic Congress (AD (AD) Advanced Peoples Democratic Alliance (DA) All Progressives Grand Alliance (FM Doga) All People’s Party (Ẹni) African Party [ar [4] Conl's Congress Congress [C] Communist Party of Nigeria (FM Sanls ( Modu (Cuse) Democratic Alternative (Da) Democratic Gailar (d) Fresh Democratic Party (f FM Al) Justice Oroko Party (Jhi) Labour Party [1] Mass Movement of Nigeria (N National Pi Con (N- National Interest Party (Ni Ni William 2019ts ( 1989 ( 2006 (of Nigeria (ng) National Democratic Party (FM Party) People's Democratic Party (PDP (PDP (PDP Peoples Fi Alliance (ppa) People Progressive (PPPP) People's Redels ( Lodu O's Salvation Party (p) (Áà) Action Alliance Social Democratic A (SDC) Party of Nigeria (s (s) Social Party (p Soko Nigeria People People’s Party (UNPPS) United Progressive (FM FM People Political People Political Young Progressive (y (y) Kunle Party (y Mouse Ọdun Ade O 2016- National Democratic Cophega Cotes) Committee ( National Con Con (NC) Democratic Party (Nigeria (D12] Grass (FM Democratic GWA | wikipedia | yo |
Unity Party of Nigeria (UPN) ló ti fìgbà kan jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tó lààmì laaka ní apá ìwò oòrùn ilẹ̀ Nàíjíríà lásìkò ìjọba àwa-arawa ẹlẹ́kejì (second republic) ní ọdún 1978-1983.. | wikipedia | yo |
Ẹgbẹ́ òṣèlú náà ló dá lórí ipò ìáájú ológbè Obábáfẹ́ Awólọ́, ẹni tí ó ti fìgbà kan jẹ́ ìlú-mọ̀ọ́ka olóṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó sì ti di ìṣèjọba mú mú lásìkò rẹ̀.. rẹ̀.. | wikipedia | yo |
Àmọ́, àníyàn ẹgbẹ́ òṣèlú náà ló dá lórí ìṣèjọba àwùjọ àwa-arawa ló mú yàtọ̀ sí àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú tó kù.. | wikipedia | yo |
Ẹgbẹ́ UPN jogún ìmọ̀ wọn lati ẹgbẹ́ òṣèlú ÀTIJỌ́ tẹ́lẹ̀ ti Action Group tí ó sì jẹ́ kí ó di ẹgbẹ́ òṣèlú fún gbogbo àwùjọ.. | wikipedia | yo |
Òun ló jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú tí ó ṣe ìgbé-lárugẹ fún ètò ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ fún gbogbo àwọn akẹ́kọ̀ọ́.àríwòye Ìjọba Ológun tí Ọ̀gágun Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ ni kí ó dá ẹgbẹ́ òṣèlú tí yóò mú ẹlẹ́yà-mẹ̀yà kúrò lágbo òṣèlú ilẹ̀ Nàìjíríà lásìkò ìjọba àwa-arawa ẹlẹ́kejì.. | wikipedia | yo |
Subẹru, The struggle for New States in Nigeria, 1976-1990, African Affairs > Vol.. | wikipedia | yo |
Monte Aguila jẹ́ ìlú kan ní tsílẹ̀.Galleryi àwọn ìlú àti abúlé ni tsile.. | wikipedia | yo |
Ile ominira je ile-ise alaja marundinlọgbọn ti wa ni iwo oorun Tafawa Balewa Square, ni Onikan ni ilu Eko.Ijoba orile-ede Britain ni o se ìdáwọ́lé yìí nipa ki o le mejilelogosan ominira orile-ede Naijiria ni odun 1960.Kon ti won ti fi agbara kun ni won fi ko ile yi, inu ile yi ni ile olori ise Olugbega wa nigba isakosoBabangida, awon eyan de mo bi ile Olugbega.. | wikipedia | yo |
Ni ọdun 1993, awọn apa kan ninu ilẹ yi Jona, lati igba ti iṣẹlẹ yi ti ṣẹlẹ ni wọn o tọju ilẹ̀ yi daradara.Awọn itọkasi.. | wikipedia | yo |
Òkè-Ìlá Òràngún (tí a ma n gé kúrú sí Òkè-Ìlá) jẹ́ ìlú àdàyé bá ní ìhà gúsù-ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti fi ìgbà kan jẹ́ olú-ìlú ẹ̀yà àwọn Ìgbómìnà-Yoruba tí à n fi orúkọ kàn án náà pè.Òkè-Ìlá jé ọ̀kan l'ara àwọn ìlú tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Osun, ní orílè-èdè Nàìjíríà.. | wikipedia | yo |
Òkè-Ìlá wà ní apá ìhà àríwá ila-oorun ilẹ̀ Yoruba ni gugu-iwọ-oorun orile-ede Naijiria.. | wikipedia | yo |
Òkè-Ìlá ní ìlú kan tí ó sunmo, èyí tí ìtàn sọ fún wa pé ìbátan rẹ ni, tí a n pe ni Ìlá Òràngún.. | wikipedia | yo |
Ìlá Òràngún wà ní ìwọ̀n ìrépọ̀ mejila (mámáì meje ati ààbò) sí ìhà ariwa-ilá-oòrùn, àwọn ọ̀gbuǹ tí ó ti ìhà ariwa wá sí pín wọn sí ìso-ìsọrí tí a mọ̀ sí Òkè-I-I-Ìlá Òràngún ni olú-ìlú fún ìjọba ìbílẹ̀ Ìfẹ́dayọ̀ ní ìpínle Ọ̀sun.. | wikipedia | yo |
Olú ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Ìfẹ́dayọ̀ wà ní ìhà ÀRÍWÁ etí ìlú náà.. | wikipedia | yo |
Àmójútó iṣé'jọba Àwọn ìlú méjèèjì yí, àti ti àwọn ìlú kéréje-kéréje pẹ̀lú àwọn ìgbèríko tí ó yí wọn ká ní on ti olú ilé-iṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Ìfẹ́dayogún jáde wá... | wikipedia | yo |
Àwọn ojogbon nínú èdè àti Litireso YorubaProfessors of the Yoruba lingistics, language, Literature & Cultures/n Orúkọ Yunifásítì1.1tus Professor Adeboye BabalolaUniversity of Lagos2.2tus Professor Ayo Bam University of Ibadan.Professor Ọladele Awóbùlúyì Adekunle Ajasin University.Professor sọpé Oyela Oyeran Obafemi Awolowo Awo.Professor Wande Abimbola Abimbola Obafemi Awolowo Awo.Professor Olatunde Olatunji University of Ibadan.Professor Akínwùmí Ìṣọ̀lá Ìṣọ̀lá Obafemi Awolowo Awo.Professor Kola Owólabí University of Ibadan.9 Adegboyega Alaba of Lagos10.Professor Aroko. Aọlá ọlá ọlá University of Lagos.Professor bádé In Àjùwon Obafemi Awolowo Awo.Professor 2016.. | wikipedia | yo |
Ilésanmí Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University13.Professor (Mrs.) Olutóyè University of Lagos14.Professor ADEBIS Ògúnṣínà University of Ìlọrin15.professor l.. | wikipedia | yo |